text
stringlengths 23
128
| clean_label
stringclasses 7
values | clean_label_id
int64 0
6
| noisy_label
stringclasses 7
values | noisy_label_id
int64 0
6
|
---|---|---|---|---|
Xenophobic Attack: Awọn ọmọ Nàìjíria tí yarí pé àwọn náà yóò gbẹ̀san | africa | 5 | africa | 5 |
Árẹ̀wá: Bákan náà ni a kò fẹ́ Atiku torí dúkìá àjọni wà tó fẹ́ tà | politics | 4 | politics | 4 |
2019 Election update: Buhari borí; ó di ààrẹ Nàìjíríà tuntun | politics | 4 | politics | 4 |
Nathaniel Samuel: Ìwádìí tí bẹ̀rẹ̀ lórí afurasí tó gbé ado olóró wọ ilé ìjọsìn Winners | nigeria | 1 | sport | 3 |
Yoruba Film: Ṣé ẹ máa wá ní Pasuma ni mo bí àwọn ọmọ mi tó ń jẹ́ Kuti fún - Jaiye | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
2020 Budget: Owóyàá lábẹ́lé àti nílẹ̀ òkèèrè nìjọba fẹ́ fi gbọ́ bùkátà ìṣúná 2020 | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Building Collapse: Ìdí tí ilé fi ń wó nìyí' | nigeria | 1 | sport | 3 |
Harry and Meghan: Mí o ṣààdédé gbé ìgbésẹ̀ láti kúrò nílé Ọba | world | 0 | world | 0 |
Wasiu Ayinde: Ó pọn dandan fún Mayegun láti ri pé àláfíà jọba | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Okunnu: Ẹnu Ayinde Barrister ni mo ti gbọ́ orúkọ 'Okunnu' kí n tó máa jẹ́ẹ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Adigunjalè ń bèérè ẹyin, ouńjẹ ati aṣọ lọ́wọ́ àwọn tí wọ́n ń jà lólè ní ìpinlẹ Niger | nigeria | 1 | world | 0 |
Pius Adesanmi: Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ èèyàn ń dárò ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Nàìjíríà tó kú nínú ìjàmbá bàálù Ethiopia | africa | 5 | nigeria | 1 |
Àwọn nnkan tó yẹ kí o mọ nípa Adekunle Akinlade ti ADM | politics | 4 | politics | 4 |
Ọọ̀ni: Ìpèníjà ààbò di ìràwọ̀ ọ̀sán tó ń ba àwa àgbà lẹ́rù | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
NIS ní àwọn kò ṣèṣẹ̀ máa fí ìwé irinnà ránṣẹ sí àwọn tó bá fẹ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
ASUU Strike: Òtítọ́ wo ló wà nínú pé ASUU tún fẹ́ yanṣẹ́lódì? | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
NLC: Ìpàdé ọjọ́ Ajé ni yóò sọ bóyá á yansẹ́ lódì | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Oyo Isese Day: Aug 20 ni ọjọ́ àkànṣe àdúrà sí Ọlọ́run àtàwọn Alálẹ̀ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Lagos Police: Tí ìrònú bá ti pọjù , ó le ṣokùnfa àìṣiṣí nǹkan ọmọkùnrin | nigeria | 1 | world | 0 |
NAFDAC: Ohun tí wọ́n fi ń se báàgì, bàtà ni wọ́n ń tà bíi ‘pọ̀ǹmọ́ | health | 2 | health | 2 |
Nigeria Presidency: Kí ló ń fa wàhálà ojojúmọ́ ní ilé Ààrẹ l'Abuja | nigeria | 1 | politics | 4 |
Gani Adams: Inú ìpèbí ni Ọ̀yọ́mèsì ti pàṣẹ kí n yan olóyè mi | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Ìbéèrè pọ̀ lórí òkú ọkùnrin kan tí ọlọ́pàá bá nínú àgbá ní Oyingbo | nigeria | 1 | world | 0 |
Ibadan Fire: Iná míràn tún ṣẹyọ nilú Ibadan | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Olè Lekki: Obìnrin méjì ni wọ́n dá lọ́nà, tọ́wọ́ ọlọ́pàá fi tẹ̀ wọ́n | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Naira Marley: Naira Marley moribọ, ilé ẹjọ́ tú ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé tí wọ́n fi kàn án ká | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Sex For Grades: Four Square Church tí ní kí olùkọ́ fásitì Pasitọ̀ Boniface lọ fìdímọ́lé | nigeria | 1 | world | 0 |
Governorship Election Update: Àfikún ìdìbò yóò wáyé nìpínlẹ̀ mẹ́fà lọ́jọ́ kẹtàlélógún oṣù yìí | politics | 4 | politics | 4 |
Busa 2019: Sadiya Umar Farouq - Obìnrin Olóṣelú tó lààmì laaka. | entertainment | 6 | politics | 4 |
Ọọni: Ilẹ̀ ifẹ̀ ní ìran Ìgbò tí ṣẹ wá kìí ṣe ilẹ̀ juu | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
UI- Ìwádìí àyẹwò nìkan ló lè sọ ohùn tó pá olùkọ́ tó kù nínú ilé to jo | health | 2 | health | 2 |
Nkechi Blessing: Ọ̀rọ̀ ìfẹ́ wa dàbí ti Romeo àti Juliet | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Dangote: Ẹ̀ yin ọmọ Nàíjíríà, ẹ máṣe sọ ìrètí nù nípa ilẹ̀ wa | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ìjọba Ekiti n gbèrò òfin tí yóò fí ìjìyà titẹ lọ́dàá jẹ àwọn afipábánilòpọ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Serena Williams: Wang tún da àlá Ife ẹ̀yẹ kẹrìnlélógùn fún Serena Williams rú | sport | 3 | nigeria | 1 |
Ikú Djxgee: DJsosogee ní olóògbé fẹ́ràn ẹbí àti ọmọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Operation Amotẹkun: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Yorùbá 'Àmọ̀tẹ́kùn' ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàrọ́ọ̀ oò jíire | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Kìnìhún fa èèyàn kan ya ní Nairobi, àdúgbò dàrú | africa | 5 | nigeria | 1 |
NCAA: A fún àwọn adarí ní ọ̀sẹ̀ méjì si láti dá wọn lóhùn | nigeria | 1 | world | 0 |
Buhari: Baba 'Go slo' ní ìṣèjọba alágbádá ti ń falẹ̀ jù fún ipinnu òun gbogbo | politics | 4 | politics | 4 |
Ondo Kidnap: Géńdé agbébọn jí adájọ́ gbé lọ ní ìpínlẹ̀ Ondo | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Foluke Daramola: Ìgbé ayé gbajúmọ̀ gbọdọ̀ ṣèwúrí fún àwọn èèyàn láti dé ibi gíga | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Kano Gorilla: Òṣìṣẹ́ 10 wọ gàù lórí ọ̀rọ̀ Ìnàkí tí wọ́n ló gbé owó tí wọn pa lásìkò ìtúnu ààwẹ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Danjuma: Ète ń lọ láti dá wàhálà sílẹ̀ láwọn ìpínlẹ̀ kan torí mọ̀kàrúrù ìbò | politics | 4 | politics | 4 |
Xenophophia: Lizzy Anjorin, Yinka Ayefele, Mercy Aigbe sọ̀rọ̀ ìtùnú | africa | 5 | entertainment | 6 |
EFCC mo dé' àti àwọn àṣà míì táwọn olóṣèlú fi dagbo rú ní 2018 | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Xenophobia: Àwọn agbófinró dúró sẹ́nu ọ̀nà àbáwọlé Palm Mall Ibadan láti dẹ́kun ìkọlù | africa | 5 | world | 0 |
Ìdìbò ọdún 2019: Atiku Abubakar kò yóju síbi ìpàdé àjùmọse àláfíà | politics | 4 | politics | 4 |
Èèyàn mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ìjàmbá ọkọ̀ akérò tó ya wọ ọjà ní Ibadan | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Iléesẹ́ ológun: Amẹrika, Italy ń tìwá lẹ́yìn láti sẹ́gun Boko Haram | world | 0 | nigeria | 1 |
Community Policing: Onímọ̀ ètò ààbò ní kìí ṣe ojúṣe ọ̀gá ólọ́pàá láti dá ọlọ́pàá agbègbè sílẹ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Operation Amotekun: Atiku ní ẹ̀ṣọ́ alábòò Amọtẹkun yóò ṣ'èrànwọ́ lórí ètò ààbò tó mẹ́hẹ | nigeria | 1 | politics | 4 |
Oluwo: Inú ìwé kíkà ni ọja ọ̀la àwọn Fulani wà | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Nigeria Election 2019: Saraki àti àwọn sẹ́nẹ́tọ̀ tó fẹ̀yìn gbálẹ̀ nínú ìdìbò ilé aṣòfin | politics | 4 | politics | 4 |
APC Governors: Ẹ̀ka aláṣẹ́ ti já agbára gbà mọ́ ìgbìmọ̀ olùdarí APC lọ́wọ́ | politics | 4 | politics | 4 |
Ethiopian Airlines crash: Èèyàn 157 dèrò ọ̀run nínú bàálú tó já | africa | 5 | africa | 5 |
Nigeria 2019 Elections: Ohun mẹ́rin tó jẹyọ nínú ọ̀rọ̀ Atiku níbi ìpàdé PDP | politics | 4 | politics | 4 |
Amojúẹ̀rọ tó ń nu bàtà fi wá oúnjẹ òòjọ́ | entertainment | 6 | health | 2 |
Nigeria 2019 Election: Fayoṣe ní EFCC ń wá owó Atiku bọ̀ wálé òun l'Ekiti | politics | 4 | politics | 4 |
Ilaro Poly: Ààrẹ ẹgbẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní ṣọ́ọ́ṣì ni òun ń lọ, àmọ́ òun tó bára òun nínú igbó fún ìbúra ẹgbẹ́ awo | nigeria | 1 | politics | 4 |
Ìwé ìrìnnà 'VISA' Amẹ́ríkà: PDP láwọn faramọ ìgbésẹ Amẹ́ríkà | world | 0 | nigeria | 1 |
Bayelsa, Kogi Election: APC ní yóò jáwe olúbori | politics | 4 | politics | 4 |
Bola Tinubu: Ìròyìn òfegè ni, Tinubu lóun ò pe Buhari ní alákatakítí ẹ̀sìn láéláé | politics | 4 | politics | 4 |
Lizzy Anjorin vs Toyin Abraham: Àwọn àgbààgbà ẹgbẹ́ òṣèré tíátà fa ìbínú yọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ìtàn Mánigbàgbé: Ayinla Ọmọwura kò kàwé, àmọ́ ó kópa sí àgbéga orin àti èdè Yorùbá | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Premier League: Man City ti fàgbà han Fulham pẹ̀lú 2-0 | sport | 3 | sport | 3 |
Yinka Ayefele fi orin ẹ ṣeun sẹ́nu lórí ilé orin tuntun rẹ̀ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Brexit: Ọ̀rọ̀ kò yé wa mọ́! | world | 0 | world | 0 |
Election Update 2019: Àwọn aráàlú ń fapá jánú lórí ìdádúró tó bá kíka èsì ìbò ààrẹ | politics | 4 | politics | 4 |
Champions league: Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù wo ni yóò tẹ̀síwájú? | sport | 3 | sport | 3 |
Olusegun Obasanjo: Ìjọba Ààrẹ Buhari kò yàtọ̀ sí ti Abacha | politics | 4 | politics | 4 |
South Africa killings: Sanwo-Olu ní àwọn ọmọ Nàìjíríà tó gbẹ̀san ìkọlù àjòjì ní South Africa ti yọ ọmọ Nàìjíríà 5000 níṣẹ́ l'Eko | africa | 5 | africa | 5 |
Fire: Ọkùnrin mẹ́fà àti obìnrin mẹrin ni wọ́n rí gbé jáde nínú ọkọ̀ akérò tó jóná | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Oyo: Ilé ẹjọ́ tó ga jù dá Seyi Makinde láre gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ | politics | 4 | politics | 4 |
Fire: Táńkà epo méjì tó forí gbárí ló fa sábàbí iná ọ̀hún | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Coronavirus: Àìsàn yíì ti ràn dé Amẹrika, Thialand àti South Korea | health | 2 | health | 2 |
Kylie Jenner ń pa $360m lọ́dún kan, tó sì ta adarí Facebook yọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Sagamu: Ògo ọjọ́ iwájú ìdílé wa ni Kazeem tí àwọn SARS ṣekúpa - Iya Kazeem Tiamiyu | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Texas Walmart shooting: Èèyàn ogún pàdánù èmi wọn ninu ìyibọ́npanìyàn El Paso | world | 0 | world | 0 |
Nigeria Election 2019:Awọn wò ní Gómìnà El Rufai n ba wi pẹlu ihalẹ 'body bag' | politics | 4 | politics | 4 |
Kidnapping: Aago méje alẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun làwọn agbégbọn dí ọ̀nà márosẹ̀ Ibadan | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Oladejo Okediji, gbajúgbajà òǹkọ̀wé Yorùbá papòdà lẹ́ni ọdún 89 | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
EFCC: Akinwumi Sorinmade ni orúkọ tí Aroke ń lo ni ilé ìfowópamọ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
World Education Day: Wo ọmọ ogún ọdún tí kò lè ka lẹ́tà ''A'' dé ''Z'' | world | 0 | entertainment | 6 |
Faye Mooney: Ìlú Eko ló ti lọ sóde àríyá ní Kaduna ni wọ́n yìnbọn fun | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ido-Ani Robbery: Àwọn adigunjalè pa ènìyàn mẹ́fà ní báńkì kan nìpínlẹ̀ Ondo | nigeria | 1 | world | 0 |
Dino Melaye: Mí ò sí lára àwọn aṣòfin tó bú Buhari | politics | 4 | politics | 4 |
Eid-il Kabir: Iléẹjọ́ f'òfin de Oluwo pé kò gbọdọ̀ darí ìrun ní 'EID' lọ́dún Iléyá | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Bayelsa Guber update: Atiku ní àwọn adájọ́ fihàn pé ọwọ́ aráàlú lagbára sì wà | politics | 4 | politics | 4 |
Sẹ́ríkí Fúlàní ní ìpínlẹ̀ Ọṣun ní kò sí ìdí fún àwọn darandaran láti kúrò l'Ọ́ṣun | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Election Tribunal: Ẹ̀rù tó ń ba APC ni wọ́n ṣe kọ̀wé sáwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ | politics | 4 | politics | 4 |
Ìtàn Mánigbàgbé: Oyenusi ní òun kò bá tí digunjalè, táwọn òbí òun bá lágbára láti rán òun níléèwé | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Bánkì tó bá kọ láti tẹlé ìlànà CBN tuntun, ₦2m ní yóò fí gbára | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Afenifere: Àsìkò tó tá tako ìkọlù darandaran nílẹ̀ Yorùbá | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Nigeria vs Seychelles: Ikọ Super Eagles bori Seychelles pẹ̀lú 3-1 nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ AFCON | sport | 3 | sport | 3 |
Food Poison: Oúnjẹ márùn-ún tó lè ṣekú pa'ni kíákíá | health | 2 | health | 2 |
Viemens Bamfo: Ọmọ ọdún méjìlá tó gbèlé kẹ́kọ̀ọ́ dì àpéwò bó tí ṣé wọ ilé ẹ́kọ́ fásítì Ghana | africa | 5 | nigeria | 1 |
Sunday Igboho: Ifayẹmi Ẹlẹbubọn ní àgbààgbà Yorùbá yẹ kó pe àpérò lórí ìmọ̀ràn Igboho láti rẹ́yìn àjínigbé | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Nigeria Swearing in 2019: Kà nípa gómìnà tuntun ni Kwara | politics | 4 | politics | 4 |
Yollywood: Lizzy Anjorin tí fi ìwé ìpẹ̀jọ́ ránsẹ́ sí Toyin Abraham | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
End of preview. Expand
in Dataset Viewer.
- Downloads last month
- 43