diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ó sì ṣe tí àwọn ẹranko
O si se ti awon eranko
Ìwé gbédègbẹ́yọ̀ The Concise Jewish Encyclopedia , sọ pé : “ Títẹ̀lé òfin àti síso ońdè mọ́ra ló ń dáàbò boni kúrò lọ́wọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù . ”
Iwe gbedegbeyo The Concise Jewish Encyclopedia , so pe : “ Titele ofin ati siso onde mora lo n daabo boni kuro lowo awon emi esu . ”
Ìkìlọ̀ ni àpẹẹrẹ wọn yìí jẹ́ fún wa pé ká mọyì òmìnira tá a ní , ká túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà , ká sì máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ . ​ — 1 Kọ́r .
Ikilo ni apeere won yii je fun wa pe ka moyi ominira ta a ni , ka tubo sun mo Jehofa , ka si maa pa awon ase re mo . ​ — 1 Kor .
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 23 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 23 ]
Ó tún máa ń ṣe àwọn kúlẹ̀kúlẹ̀ mìíràn , irú bíi , bóyá wọ́n ti mọ ẹnì kan mọ́ àwọn ọ̀daràn tẹ́lẹ̀ rí , bóyá ẹnì kan ti hu ìwàkiwà kan rí ní iléeṣẹ́ ọkọ̀ òfuurufú náà , tàbí tó hùwà àìdáa kan sí àwọn òṣìṣẹ́ wọn níbẹ̀ , tàbí bóyá ó ti bà wọ́n ní nǹkan jẹ́ rí .
O tun maa n se awon kulekule miiran , iru bii , boya won ti mo eni kan mo awon odaran tele ri , boya eni kan ti hu iwakiwa kan ri ni ileese oko ofuurufu naa , tabi to huwa aidaa kan si awon osise won nibe , tabi boya o ti ba won ni nnkan je ri .
búra, dájúdájú ẹ sì wà nínú àṣìṣe
bura, dajudaju e si wa ninu asise
Kí Nìdí Tí Jèhófà Fi Lu Úsà Pa ?
Ki Nidi Ti Jehofa Fi Lu Usa Pa ?
Kọ̀ǹpútà ò lè ṣe ìtumọ̀ tó dára .
Konputa o le se itumo to dara .
Bí àpẹẹrẹ , lórílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà , ọ̀pọ̀ lára àwọn tó ti fẹ̀yìn tì ló tún ti padà sẹ́nu iṣẹ́ nítorí pé wọ́n fi owó ìfẹ̀yìntì wọn dù wọ́n .
Bi apeere , lorile - ede Amerika , opo lara awon to ti feyin ti lo tun ti pada senu ise nitori pe won fi owo ifeyinti won du won .
Gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin pípé pẹ̀lú ìjìnlẹ̀ òye àrà ọ̀tọ̀ tí Ọlọ́run fún un , ó lè rí ọkàn .
Gege bi okunrin pipe pelu ijinle oye ara oto ti Olorun fun un , o le ri okan .
láti inú ẹ̀yà Aṣeri, ó rán Seturu, ọmọ Mikaeli;
lati inu eya Aseri, o ran Seturu, omo Mikaeli;
Níkẹyìn , alúfàá náà sọ fún un pé ó jẹ́ arẹwà ọmọbìnrin tó ní làákàyè , nítorí náà kó kọ́kọ́ jayé orí rẹ̀ nísinsìnyí tó ṣì lè ṣe bẹ́ẹ̀ , lẹ́yìn náà ó lè wá máa sin Ọlọ́run nígbà tó bá darúgbó .
Nikeyin , alufaa naa so fun un pe o je arewa omobinrin to ni laakaye , nitori naa ko koko jaye ori re nisinsinyi to si le se bee , leyin naa o le wa maa sin Olorun nigba to ba darugbo .
• Àwọn ohun wo la lè ṣe kí Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ má bàa borí wa ?
• Awon ohun wo la le se ki Satani atawon emi esu re ma baa bori wa ?
Ẹ̀yin ọmọ mi, mò ń kọ ìwé yìí si yín, kí ẹ má baà dẹ́ṣẹ̀. Bí ẹnikẹ́ni bá wá dẹ́ṣẹ̀, a ní alágbàwí kan pẹlu Baba tíí ṣe Jesu Kristi olódodo.
Eyin omo mi, mo n ko iwe yii si yin, ki e ma baa dese. Bi enikeni ba wa dese, a ni alagbawi kan pelu Baba tii se Jesu Kristi olododo.
Wọ́n gbé e sípò ńlá , wọ́n sì tún máa ń fún un láyè dáadáa níbi iṣẹ́ .
Won gbe e sipo nla , won si tun maa n fun un laye daadaa nibi ise .
Gbogbo nǹkan ni a kà, tí a sì wọ̀n, gbogbo iye ìwọ̀n ni a sì ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ sínú ìwé ní ìgbà náà.
Gbogbo nnkan ni a ka, ti a si won, gbogbo iye iwon ni a si se akosile re sinu iwe ni igba naa.
Ìtàn Ìdílé láti Ọ̀dọ̀ Baba Ńlá ti Saulu ará Benjamini.
Itan Idile lati Odo Baba Nla ti Saulu ara Benjamini.
․ ․ ․ ․ ․ àwọn ohun tí mo nífẹ̀ẹ́ sí
. . . . . awon ohun ti mo nifee si
Ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ yìí kìí ṣẹlẹ̀ ní ìgbésẹ̀ kan ṣùgbọn ó maa ń kọ́kọ́ jásí dihydropentacene tí wọ́n maa ń yọ hydrogen kúrò nínú rẹ̀ ní ìgbésẹ̀ kejì pẹ̀lú copper gẹ́gẹ́ bí amúlọsíwájú bá ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́.[4]
Idapapo sise yii kii sele ni igbese kan sugbon o maa n koko jasi dihydropentacene ti won maa n yo hydrogen kuro ninu re ni igbese keji pelu copper gege bi amulosiwaju ba idapapo sise.[4]
Èrò yìí ti dá ọ̀pọ̀ wàhálà sílẹ̀ .
Ero yii ti da opo wahala sile .
Ṣé Ohun Tí Wọ́n Fi Kọ́ Ẹ Láti Kékeré Ni ?
Se Ohun Ti Won Fi Ko E Lati Kekere Ni ?
( Ka Lúùkù 2 : 52 . )
( Ka Luuku 2 : 52 . )
Àti pẹ̀lú pé ìmọ̀ nípa àwọn
Ati pelu pe imo nipa awon
ṣámrì
samri
Àwọn ará tẹ̀ lé àwọn ìtọ́sọ́nà wọn , èyí sì mú kí ìjọ máa “ bá a lọ ní fífìdímúlẹ̀ gbọn - in nínú ìgbàgbọ́ àti ní pípọ̀ sí i ní iye láti ọjọ́ dé ọjọ́ . ”
Awon ara te le awon itosona won , eyi si mu ki ijo maa " ba a lo ni fifidimule gbon - in ninu igbagbo ati ni pipo si i ni iye lati ojo de ojo . "
Olúwa rẹ ni tití di àsìkò tí a ti
Oluwa re ni titi di asiko ti a ti
Ara fífaṣẹ́lénilọ́wọ́ ni yíyan iṣẹ́ àti wíwo bí iṣẹ́ náà ṣe ń tẹ̀ síwájú sí
Ara fifaselenilowo ni yiyan ise ati wiwo bi ise naa se n te siwaju si
Lẹ́yìn náà kó wá jẹ́ kó rí ewu tẹ̀mí tó wà nínú gbígba iṣẹ́ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ rí yẹn .
Leyin naa ko wa je ko ri ewu temi to wa ninu gbigba ise to sese ri yen .
GẸ́GẸ́ BÍ ESTHER GAITÁN ṢE SỌ Ọ́
GEGE BI ESTHER GAITAN SE SO O
Ọ̀rọ̀ náà “ ọ̀rá ” tí a lò níhìn - ín la lò lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ ó sì dúró fún ẹran tó dára jù lọ nínú agbo ẹran .
Oro naa “ ora ” ti a lo nihin - in la lo lona isapeere o si duro fun eran to dara ju lo ninu agbo eran .
Ọ̀pọ̀ lára irú àwọn bẹ́ẹ̀ ti ronú pìwà dà wọ́n sì ti pa dà ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Baba wa ọ̀run tó jẹ́ aláàánú .
Opo lara iru awon bee ti ronu piwa da won si ti pa da ni ajose to daa pelu Baba wa orun to je alaaanu .
Ó sọ̀rọ̀ nípa ìjọba kan tí Ọlọ́run ti ṣètò ní ọ̀run , tó máa rọ́pò ìjọba èèyàn àti ètò ọ̀rọ̀ ajé tí kò lè yanjú ìṣòro àwọn èèyàn , èyí tó ń mú kí wọ́n máa wọ́de láti jà fún ẹ̀tọ́ wọn .
O soro nipa ijoba kan ti Olorun ti seto ni orun , to maa ropo ijoba eeyan ati eto oro aje ti ko le yanju isoro awon eeyan , eyi to n mu ki won maa wode lati ja fun eto won .
Olùgbàrònúpìwàdà, Alaàánú
Olugbaronupiwada, Alaaanu
Àwa gẹ́gẹ́ bí Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń gbé e lárugẹ nítorí àwọn iṣẹ́ àrà tó ṣe , bíi dídá Ísírẹ́lì nídè kúrò nínú ìgbèkùn Íjíbítì àti bí oyún Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n ṣe ṣẹlẹ̀ lọ́nà ìyanu .
Awa gege bi Elerii Jehofa n gbe e laruge nitori awon ise ara to se , bii dida Isireli nide kuro ninu igbekun Ijibiti ati bi oyun Omo re owon se sele lona iyanu .
Àwọn òǹṣèwádìí tiẹ̀ ti fojú bù ú pé iyàn jíjà lórí owó ló máa ń fà á tí mẹ́sàn - án fi ń tú ká lára ìgbéyàwó mẹ́wàá .
Awon onsewadii tie ti foju bu u pe iyan jija lori owo lo maa n fa a ti mesan - an fi n tu ka lara igbeyawo mewaa .
Lóde òní , onírúurú ọ̀nà làwọn èèyàn ń gbà fi hàn pé àwọn jẹ́ agbéraga .
Lode oni , oniruuru ona lawon eeyan n gba fi han pe awon je agberaga .
3 Ṣé Àwọn Áńgẹ́lì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ ?
3 Se Awon Angeli Le Ran E Lowo ?
Pọ́ọ̀lù kọ̀wé pé : “ Bí ìmúratán bá kọ́kọ́ wà , ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà ní pàtàkì ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí ènìyàn ní , kì í ṣe ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí ènìyàn kò ní . ” — 2 Kọ́ríńtì 8 : 12 .
Poolu kowe pe : " Bi imuratan ba koko wa , o se itewogba ni pataki ni ibamu pelu ohun ti eniyan ni , ki i se ni ibamu pelu ohun ti eniyan ko ni . " -- 2 Korinti 8 : 12 .
Ọ̀rọ̀ kan wà tó yẹ ká fi ọwọ́ pàtàkì mú , ìyẹn ni bí a ó ṣe máa ti ipò Jèhófà gẹ́gẹ́ bí ọba aláṣẹ ayé àtọ̀run lẹ́yìn .
Oro kan wa to ye ka fi owo pataki mu , iyen ni bi a o se maa ti ipo Jehofa gege bi oba alase aye atorun leyin .
Ẹ Máa “ Fi Ẹnu Kan ” Yin Ọlọ́run Lógo
E Maa " Fi Enu Kan " Yin Olorun Logo
Tó o bá fẹ́ fi sọ̀wédowó ránṣẹ́ , ọ̀rọ̀ náà , “ Watch Tower ” ni kó o kọ sórí rẹ̀ kó lè ṣeé ṣe fún wa láti rí owó náà gbà .
To o ba fe fi sowedowo ranse , oro naa , “ Watch Tower ” ni ko o ko sori re ko le see se fun wa lati ri owo naa gba .
Aláàánú ará Samáríà yẹn kò yí ayé yìí padà o , àmọ́ ó mú àyípadà rere bá ayé ẹnì kan .
Alaaanu ara Samaria yen ko yi aye yii pada o , amo o mu ayipada rere ba aye eni kan .
Nígbà míì , ó lè jẹ́ torí pé ibi tẹ́ ẹ̀ ń gbé jìnnà síra .
Nigba mii , o le je tori pe ibi te e n gbe jinna sira .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tó ń sọ èdè náà ò tó nǹkan tá a bá fi wé èdè míì , síbẹ̀ wọ́n ṣì nílò ìhìn rere náà ní èdè wọn . ”
Bo tile je pe awon to n so ede naa o to nnkan ta a ba fi we ede mii , sibe won si nilo ihin rere naa ni ede won . "
Ẹ̀kọ́ pàtàkì méjì kan wà tá a lè rí kọ́ nínú 2 Sámúẹ́lì orí 7 .
Eko pataki meji kan wa ta a le ri ko ninu 2 Samueli ori 7 .
Ta ni yóò wá ni àwọn ohun tí ìwọ tò jọ pa mọ́ ? ’
Ta ni yoo wa ni awon ohun ti iwo to jo pa mo ? ’
Ìlérí táwọn èèyàn ń ṣe náà ńkọ́ ?
Ileri tawon eeyan n se naa nko ?
Ṣe àlàyé yékéyéké fún dókítà rẹ nípa àwọn ibi tó o ti rìnrìn àjò lọ
Se alaye yekeyeke fun dokita re nipa awon ibi to o ti rinrin ajo lo
▪ Oúnjẹ á máa tètè sú u , á máa ṣèrànrán lójú oorun , ó sì lè máà rí oorun sùn dáadáa
# Ounje a maa tete su u , a maa seranran loju oorun , o si le maa ri oorun sun daadaa
Ọ̀kẹ́ àìmọye ìránṣẹ́ Jèhófà ni irú èyí ti ṣẹlẹ̀ sí .
Oke aimoye iranse Jehofa ni iru eyi ti sele si .
Jíròrò ọ̀rọ̀ yìí pẹ̀lú àwọn òbí rẹ .
Jiroro oro yii pelu awon obi re .
( Ka Hébérù 13 : 5 . )
( Ka Heberu 13 : 5 . )
àní, àkókò ń bọ̀, tí ẹnikẹ́ni tí ó bá pa yín, yóò rò pé òun ń ṣe ìsìn fún Ọlọ́run
ani, akoko n bo, ti enikeni ti o ba pa yin, yoo ro pe oun n se isin fun Olorun
nígbà tí ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ń tàn sí mi lórí,tí mo kọjá ninu òkùnkùn pẹlu ìmọ́lẹ̀ rẹ̀;
nigba ti imole re n tan si mi lori,ti mo koja ninu okunkun pelu imole re;
Ó dá Ábúráhámù lójú gan - an pé Ọlọ́run lágbára láti jí Ísákì dìde , tó bá gba pé kó ṣe bẹ́ẹ̀ , láti lè mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ .
O da Aburahamu loju gan - an pe Olorun lagbara lati ji Isaki dide , to ba gba pe ko se bee , lati le mu ileri re se .
Wọ́n tún ń jèrè gọbọi látara òwò òrépèté tí wọ́n máa ń ṣe pẹ̀lú àwọn ará Íjíbítì àti Gíríìsì .
Won tun n jere goboi latara owo orepete ti won maa n se pelu awon ara Ijibiti ati Giriisi .
Gbogbo nǹkan wọnyi ni ẹ ní, tí ẹ sì ní lọpọlọpọ: igbagbọ, ọ̀rọ̀ sísọ, ìmọ̀, ati ìtara ní ọ̀nà gbogbo, bẹ́ẹ̀ náà ni ìfẹ́ tí ẹ ní sí wa. A fẹ́ kí ìtara yín túbọ̀ pọ̀ sí i nípa ṣíṣe iṣẹ́ ìfẹ́ pẹlu.
Gbogbo nnkan wonyi ni e ni, ti e si ni lopolopo: igbagbo, oro siso, imo, ati itara ni ona gbogbo, bee naa ni ife ti e ni si wa. A fe ki itara yin tubo po si i nipa sise ise ife pelu.
Bíbélì sọ pé “ àwọn àṣẹ rẹ̀ kì í ṣe ẹrù ìnira . ”
Bibeli so pe " awon ase re ki i se eru inira . "
Nítorí èmi yóò da omi sí ilẹ̀ tí ń pòǹgbẹ àti àwọn odò ni ilẹ̀ gbígbẹ
Nitori emi yoo da omi si ile ti n pongbe ati awon odo ni ile gbigbe
Sólómónì ọba sì dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé, Èéṣe tí ìwọ fi béèrè Ábíságì ará Súnémù fún Àdóníjà! Ìwọ ìbá sì béèrè ìjọba fún un pẹ̀lú nítorí ẹ̀gbọ́n mi ni í ṣe, fún òun pàápàá àti fún Ábíátarì àlùfáà àti fun Jóábù ọmọ Sérúíà! Nígbà náà ni Sólómónì ọba fi Olúwa búra pé
Solomoni oba si da iya re lohun pe, Eese ti iwo fi beere Abisagi ara Sunemu fun Adonija! Iwo iba si beere ijoba fun un pelu nitori egbon mi ni i se, fun oun paapaa ati fun Abiatari alufaa ati fun Joabu omo Seruia! Nigba naa ni Solomoni oba fi Oluwa bura pe
A gbàdúrà pé kí Jèhófà jẹ́ kí gbogbo ètò ọjọ́ náà yọrí sí rere .
A gbadura pe ki Jehofa je ki gbogbo eto ojo naa yori si rere .
Bí ẹkùn ilẹ̀ náà bá ṣe dá dúró sí ni àwọn ìyàtọ̀ náà ṣe lè pọ̀ tó .
Bi ekun ile naa ba se da duro si ni awon iyato naa se le po to .
Ńṣe ni Jèhófà fi jíjí tó jí Ọmọ rẹ̀ dìde ṣe ẹ̀rí pé , ìrètí àjíǹde tí gbogbo àwọn olóòótọ́ ní máa nímùúṣẹ dájúdájú .
Nse ni Jehofa fi jiji to ji Omo re dide se eri pe , ireti ajinde ti gbogbo awon oloooto ni maa nimuuse dajudaju .
Ará, ẹ má máa ṣe bí ọmọde ninu èrò yín. Ó yẹ kí ẹ dàbí ọmọde tí kò mọ ibi, ṣugbọn kí ẹ jẹ́ àgbàlagbà ninu èrò yín.
Ara, e ma maa se bi omode ninu ero yin. O ye ki e dabi omode ti ko mo ibi, sugbon ki e je agbalagba ninu ero yin.
Wo Ilé Ìṣọ́ March 15 , 2012 , ojú ìwé 30 àti 31 .
Wo Ile Iso March 15 , 2012 , oju iwe 30 ati 31 .
Ibi ìtẹ̀bọmi ìlú Timgad fi bí ẹ̀sìn Kristẹni ṣe gbilẹ̀ nígbà yẹn hàn
Ibi itebomi ilu Timgad fi bi esin Kristeni se gbile nigba yen han
Bí wọ́n bá ti ṣe inúnibíni sí mi , wọn yóò ṣe inúnibíni sí yín pẹ̀lú . ”
Bi won ba ti se inunibini si mi , won yoo se inunibini si yin pelu . "
Helikati àti Rehobu, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọ́n jẹ́ ìlú mẹ́rin;
Helikati ati Rehobu, pelu ile papa oko won je ilu merin;
àkọ́bi
akobi
Ẹni tí ó dúró gbọn - in gbọn - in fún òdodo wà ní ìlà fún ìyè , ṣùgbọ́n ẹni tí ń lépa ohun búburú wà ní ìlà fún ikú ara rẹ̀ .
Eni ti o duro gbon - in gbon - in fun ododo wa ni ila fun iye , sugbon eni ti n lepa ohun buburu wa ni ila fun iku ara re .
Nítorí náà , nígbà tó o bá kẹ́kọ̀ọ́ ohun tó wà nínú Ìwé Mímọ́ àtàwọn ìtẹ̀jáde Kristẹni tàbí nígbà tó o bá gbọ́ ìbáwí tá a fúnni ní ìpàdé ìjọ , àpéjọ àkànṣe , àpéjọ àyíká tàbí àpéjọ àgbègbè àwọn èèyàn Jèhófà , fi ìbáwí èyíkéyìí tó o bá rí gbà sọ́kàn .
Nitori naa , nigba to o ba kekoo ohun to wa ninu Iwe Mimo atawon itejade Kristeni tabi nigba to o ba gbo ibawi ta a funni ni ipade ijo , apejo akanse , apejo ayika tabi apejo agbegbe awon eeyan Jehofa , fi ibawi eyikeyii to o ba ri gba sokan .
Mo ti mọ béèyàn ṣe ń ṣọ́ owó ná , mo sì lè dá gbé ìnáwó ìrìn àjò mi fúnra mi .
Mo ti mo beeyan se n so owo na , mo si le da gbe inawo irin ajo mi funra mi .
1 Máa Ronú Nípa Àbájáde Àwọn Ìpinnu Rẹ
1 Maa Ronu Nipa Abajade Awon Ipinnu Re
Àwọn kan rò pé ó lé koko mọ́ mi , àmọ́ , mo kọ́ ohun púpọ̀ lára rẹ̀ .
Awon kan ro pe o le koko mo mi , amo , mo ko ohun pupo lara re .
Nítorí náà, mo dàbí kòkòrò ajẹnirun sí Efuraimu, ati bí ìdíbàjẹ́ sí Juda.
Nitori naa, mo dabi kokoro ajenirun si Efuraimu, ati bi idibaje si Juda.
Bẹ́ẹ̀ ni o , gbogbo àwọn ọ̀rúndún tó kọjá làwọn èèyàn tí iye wọn ò lóǹkà ti lo òmìnira wọn láti jọ́sìn ẹni tó wù wọ́n , wọ́n sì fi òmìnira yìí yàn láti jọ́sìn Jèhófà Ọlọ́run . — Jóṣúà 24 : 15 .
Bee ni o , gbogbo awon orundun to koja lawon eeyan ti iye won o lonka ti lo ominira won lati josin eni to wu won , won si fi ominira yii yan lati josin Jehofa Olorun . -- Josua 24 : 15 .
“Tàbí bí mo bá jẹ́ kí ẹranko búburú gba orílẹ̀-èdè náà kọjá, tí wọn sì bà á jẹ́ tó bẹ́ẹ̀ tí ó di ahoro, tí kò sí ẹni tó le gba ibẹ̀ kọjá torí ẹranko búburú yìí,
"Tabi bi mo ba je ki eranko buburu gba orile-ede naa koja, ti won si ba a je to bee ti o di ahoro, ti ko si eni to le gba ibe koja tori eranko buburu yii,
Tó o bá jẹ́ ìránṣẹ́ Jèhófà lọ́kùnrin tó o sì ti ṣe ìrìbọmi , kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti máa wá àǹfààní iṣẹ́ ìsìn ?
To o ba je iranse Jehofa lokunrin to o si ti se iribomi , ki lo le ran e lowo lati maa wa anfaani ise isin ?
Níwọ̀n bó ti dá a lójú pé “ ayọ̀ púpọ̀ wà nínú fífúnni ju èyí tí ó wà nínú rírígbà lọ , ” ó sọ pé : “ Mo máa ń gbìyànjú láti ṣe nǹkan fáwọn ẹlòmíràn , mi ò sì ń retí pé kí wọ́n san án pa dà .
Niwon bo ti da a loju pe “ ayo pupo wa ninu fifunni ju eyi ti o wa ninu ririgba lo , ” o so pe : “ Mo maa n gbiyanju lati se nnkan fawon elomiran , mi o si n reti pe ki won san an pa da .
Nígbà tí oúnjẹ kò sí mọ́ ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti, àwọn eniyan náà kígbe tọ Farao lọ fún oúnjẹ. Farao sọ fún gbogbo wọn pé, “Ẹ tọ Josẹfu lọ, ohunkohun tí ó bá wí fun yín ni kí ẹ ṣe.” kí ẹ lè máa bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun yín, ẹ̀yin ati arọmọdọmọ yín, kí ẹ lè máa tẹ̀lé àwọn ìlànà ati òfin tí mo fun yín lónìí, ní gbogbo ọjọ́ ayé yín, kí ẹ lè pẹ́ láyé. Mo fi òrùka sí ọ nímú, mo fi yẹtí sí ọ létí, mo sì fi adé tí ó lẹ́wà dé ọ lórí. Delila bá mú okùn titun, ó fi dè é, ó sì wí fún un pé, “Samsoni, àwọn ará Filistia dé!” Àwọn tí wọ́n sápamọ́ sì wà ninu yàrá inú. Ṣugbọn Samsoni fa okùn náà já bí ẹni pé fọ́nrán òwú kan ni.Ìwọ̀nba ẹ̀yin tí ẹ bá ṣẹ́kù, kíkú ni ẹ óo máa kú sára lórí ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín, nítorí àìdára yín ati ti àwọn baba yín.Ìyẹn ni pé kì í ṣe ìwọ ni ará Ijipti tí ó dá rúkèrúdò sílẹ̀ láìpẹ́ yìí, tí ó kó ẹgbaaji (4000) àwọn agúnbẹ lẹ́yìn lọ sí aṣálẹ̀?”Òpópónà kan yóo wà níbẹ̀,a óo máa pè é ní Ọ̀nà Ìwà Mímọ́;nǹkan aláìmọ́ kan kò ní gba ibẹ̀ kọjá,àwọn aláìgbọ́n kò sì ní dẹ́ṣẹ̀ níbẹ̀.98. Nítorí náà wọn (Ya Juju àti
Nigba ti ounje ko si mo ni gbogbo ile Ijipti, awon eniyan naa kigbe to Farao lo fun ounje. Farao so fun gbogbo won pe, “E to Josefu lo, ohunkohun ti o ba wi fun yin ni ki e se.” ki e le maa beru OLUWA Olorun yin, eyin ati aromodomo yin, ki e le maa tele awon ilana ati ofin ti mo fun yin lonii, ni gbogbo ojo aye yin, ki e le pe laye. Mo fi oruka si o nimu, mo fi yeti si o leti, mo si fi ade ti o lewa de o lori. Delila ba mu okun titun, o fi de e, o si wi fun un pe, “Samsoni, awon ara Filistia de!” Awon ti won sapamo si wa ninu yara inu. Sugbon Samsoni fa okun naa ja bi eni pe fonran owu kan ni.Iwonba eyin ti e ba seku, kiku ni e oo maa ku sara lori ile awon ota yin, nitori aidara yin ati ti awon baba yin.Iyen ni pe ki i se iwo ni ara Ijipti ti o da rukerudo sile laipe yii, ti o ko egbaaji (4000) awon agunbe leyin lo si asale?”Opopona kan yoo wa nibe,a oo maa pe e ni Ona Iwa Mimo;nnkan alaimo kan ko ni gba ibe koja,awon alaigbon ko si ni dese nibe.98. Nitori naa won (Ya Juju ati
Àwọn bàbà àti irin tó wà nílẹ̀ pọ̀ débi pé wọn ò ṣeé wọ̀n mọ́ .
Awon baba ati irin to wa nile po debi pe won o see won mo .
“ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣi afọ́jú lọ́nà.’ “Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’
" 'Eni ifibu ni enikeni ti o ba si afoju lona.' "Gbogbo eniyan yoo si dahun pe, 'Amin.'
Ó pín ilẹ̀ wọn fún àwọn eniyan rẹ̀,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;
O pin ile won fun awon eniyan re,nitori pe ife re ti ki i ye wa titi lae;
padà, kí o sì mú àwọn arakùnrin rẹ padà, kí àánú àti òtítọ́ Olúwa wà pẹ̀lú rẹ
pada, ki o si mu awon arakunrin re pada, ki aanu ati otito Oluwa wa pelu re
Ṣé wàá fẹ́ mọ̀ sí i nípa ìlérí tá a gbé ka Bíbélì yìí ?
Se waa fe mo si i nipa ileri ta a gbe ka Bibeli yii ?
Ṣe é nígbà ti ó wà ní ọ̀nà pẹ̀lú rẹ, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò fà ọ́ lé onídajọ lọ́wọ́, onídájọ́ yóò sí fá ọ lé àwọn ẹ̀sọ́ lọ́wọ́, wọ́n a sì sọ ọ́ sínú túbú
Se e nigba ti o wa ni ona pelu re, bi bee ko yoo fa o le onidajo lowo, onidajo yoo si fa o le awon eso lowo, won a si so o sinu tubu
Gbogbo ohun tó ti ṣẹlẹ̀ láàárín àkókò tó ti kọjá lọ ti fi hàn pé Èṣù ò tíì rí gbogbo èèyàn pátá yí kúrò nínú sísin Ọlọ́run tòótọ́ .
Gbogbo ohun to ti sele laaarin akoko to ti koja lo ti fi han pe Esu o tii ri gbogbo eeyan pata yi kuro ninu sisin Olorun tooto .
Àmọ́ lọ́lá Jèhófà , wọ́n lè ṣera wọn lọ́kan , kí wọ́n sì láyọ̀ .
Amo lola Jehofa , won le sera won lokan , ki won si layo .
Ó ń tu ọkàn mi lára . . . .
O n tu okan mi lara . . . .
Ta tún ni Ọlọrun, bíkòṣe OLUWA?Àbí, ta ni àpáta, àfi Ọlọrun wa?
Ta tun ni Olorun, bikose OLUWA?Abi, ta ni apata, afi Olorun wa?
mo fi bẹrẹ si i pa ero ati fi i şe aya, àkóko ti mo si n ronú báyìí náà nỉ àìsàn kan gbé e sanlệ orí àìsàn náà ló sỉ kú lé.
mo fi bere si i pa ero ati fi i se aya, akoko ti mo si n ronu bayii naa ni aisan kan gbe e sanle ori aisan naa lo si ku le.
kédámù
kedamu
Tó bá wà , kọ́ àwọn ọmọ rẹ bó ṣe yẹ kí wọ́n máa ṣe ohun náà títí dìgbà tí wàá rí i pé wọ́n lè dá a ṣe .
To ba wa , ko awon omo re bo se ye ki won maa se ohun naa titi digba ti waa ri i pe won le da a se .
Odindi oṣù márùn - ún gbáko ni Ferdinand lò látìmọ́lé , gbogbo ìgbà ni wọ́n sì ń halẹ̀ mọ́ ọn pé àwọn máa fìbọn fọ́ orí ẹ̀ .
Odindi osu marun - un gbako ni Ferdinand lo latimole , gbogbo igba ni won si n hale mo on pe awon maa fibon fo ori e .
Òótọ́ la máa ń gbóríyìn fún ẹni tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n o , àmọ́ òwe tó kàn báyìí jẹ́ ká mọ bi ìwà ìrẹ̀lẹ̀ ti ṣe pàtàkì tó .
Ooto la maa n gboriyin fun eni to je ologbon o , amo owe to kan bayii je ka mo bi iwa irele ti se pataki to .
Irú àwọn ìyá bẹ́ẹ̀ lè ti kọ ọkọ wọn sílẹ̀ , ó lè jẹ́ pé ńṣe ni ọkọ wọn kú , tàbí kó jẹ́ pé wọn ò tiẹ̀ lọ́kọ rí .
Iru awon iya bee le ti ko oko won sile , o le je pe nse ni oko won ku , tabi ko je pe won o tie loko ri .
( àtúntẹ̀ ti ọdún 2006 ) , ojú ìwé 250 àti 251 , ìpínrọ̀ 13 àti 14 .
( atunte ti odun 2006 ) , oju iwe 250 ati 251 , ipinro 13 ati 14 .
Àtọkùnrin àtobìnrin ni ìkìlọ̀ yìí wà fún o .
Atokunrin atobinrin ni ikilo yii wa fun o .
Àwọn Kristẹni àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ ń pàdé pọ̀ láwọn ilé àdáni
Awon Kristeni akokobere n pade po lawon ile adani
Ká ní o ò tiẹ̀ wá mọ̀ nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ rárá , àwọn ohun tí wàláà Gésérì sọ nípa rẹ̀ á jẹ́ kó o lè máa fojú inú rí irú àwọn nǹkan bẹ́ẹ̀ nígbà tó o bá ń ka Bíbélì , ìyẹn á jẹ́ kóhun tó ò ń kà túbọ̀ yé ọ , kó sì túbọ̀ nítumọ̀ sí ọ .
Ka ni o o tie wa mo nipa ise agbe rara , awon ohun ti walaa Geseri so nipa re a je ko o le maa foju inu ri iru awon nnkan bee nigba to o ba n ka Bibeli , iyen a je kohun to o n ka tubo ye o , ko si tubo nitumo si o .