diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ṣùgbọ́n ẹ kíyèsĩ, ẹyin ti lọ,
Sugbon e kiyesi, eyin ti lo,
Lẹ́nu àìpẹ́ yìí , wọ́n ṣe ìwádìí kan lórílẹ̀ - èdè Kánádà nínú èyí tí wọ́n ti kíyè sí àwọn abiyamọtí àìsàn yìí ń ṣe àwọn ọmọ wọn .
Lenu aipe yii , won se iwadii kan lorile - ede Kanada ninu eyi ti won ti kiye si awon abiyamoti aisan yii n se awon omo won .
Àwọn Kristẹni ni Pọ́ọ̀lù pè ní “ àwọn ènìyàn Ọlọ́run . ”
Awon Kristeni ni Poolu pe ni “ awon eniyan Olorun . ”
Ọdún mélòó kan lẹ́yìn tí wọ́n dá ìjọ Éfésù sílẹ̀ ni Pọ́ọ̀lù kọ lẹ́tà rẹ̀ sí wọn .
Odun meloo kan leyin ti won da ijo Efesu sile ni Poolu ko leta re si won .
Ó parí àkàwé náà pé : “ Àwọn wọ̀nyí [ àwọn ewúrẹ́ ] yóò sì lọ sínú ìkékúrò àìnípẹ̀kun , ṣùgbọ́n àwọn olódodo sínú ìyè àìnípẹ̀kun . ” — Mát .
O pari akawe naa pe : " Awon wonyi [ awon ewure ] yoo si lo sinu ikekuro ainipekun , sugbon awon olododo sinu iye ainipekun . " -- Mat .
Alágàbàgebè ! ”
Alagabagebe ! ”
Ẹ ṣe akiyesi ìṣe àwọn ọmọ Israẹli. Ṣebí àwọn tí ń jẹ ẹbọ ń jẹ ninu anfaani lílo pẹpẹ ìrúbọ fún ìsìn Ọlọrun?
E se akiyesi ise awon omo Israeli. Sebi awon ti n je ebo n je ninu anfaani lilo pepe irubo fun isin Olorun?
6 , 7 .
6 , 7 .
Ìfojúsọ́nà Tó Mọ Níwọ̀n , 8 / 1
Ifojusona To Mo Niwon , 8 / 1
Nítorí ẹ óo fẹsẹ̀ kọ lojumọmọ, ẹ̀yin wolii pàápàá yóo kọsẹ̀ lóru, n óo sì pa Israẹli, ìyá yín run.
Nitori e oo fese ko lojumomo, eyin wolii paapaa yoo kose loru, n oo si pa Israeli, iya yin run.
A máa ń ní irú àǹfààní yìí ní àwọn ìpàdé , nígbà tá a bá wà lóde ẹ̀rí , níbi àpèjẹ àti nígbà tá a bá ń rìnrìn àjò .
A maa n ni iru anfaani yii ni awon ipade , nigba ta a ba wa lode eri , nibi apeje ati nigba ta a ba n rinrin ajo .
Ó bá dá Batiṣeba lóhùn, ó ní, “Jọ̀wọ́ bá mi bẹ Solomoni ọba, kí ó fún mi ní Abiṣagi, ará Ṣunemu, kí n fi ṣe aya. Mo mọ̀ pé kò ní kọ̀ sí ọ lẹ́nu.”
O ba da Batiseba lohun, o ni, “Jowo ba mi be Solomoni oba, ki o fun mi ni Abisagi, ara Sunemu, ki n fi se aya. Mo mo pe ko ni ko si o lenu.”
Bó tilẹ̀ rí bẹ́ẹ̀ , kí ohun tá à ń sọ bà a lè ṣe kedere , a ó máa sọ̀rọ̀ bíi pé ọkùnrin lẹni tó ń fìyà jẹni .
Bo tile ri bee , ki ohun ta a n so ba a le se kedere , a o maa soro bii pe okunrin leni to n fiya jeni .
Ọ̀tẹ̀ sí Jerusalẹmu.
Ote si Jerusalemu.
[ Àpótí / Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 7 ]
[ Apoti / Awon aworan to wa ni oju iwe 7 ]
Báwo Ni Wọ́n Ṣe To Ìwé Inú Bíbélì ?
Bawo Ni Won Se To Iwe Inu Bibeli ?
Lẹ́yìn - ọ̀ - rẹyìn , nígbà tí alábòójútó arìnrìn - àjò wa bẹ̀ wá wò , mo béèrè lọ́wọ́ ẹ̀ nípa tàwọn ẹbí mi tí mo fẹ́ padà lọ ràn lọ́wọ́ .
Leyin - o - reyin , nigba ti alaboojuto arinrin - ajo wa be wa wo , mo beere lowo e nipa tawon ebi mi ti mo fe pada lo ran lowo .
ó ní ìrẹ̀lẹ̀, ó sì ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àní ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
o ni irele, o si n gun ketekete, ani omo ketekete
Ó wá sọ pé : “ Sọ fún ìyàwó ẹ pé kó fi se ìrẹsì aládùn fún ẹ , kó má ṣe jẹ́ kí iná pọ̀ jù . ”
O wa so pe : " So fun iyawo e pe ko fi se iresi aladun fun e , ko ma se je ki ina po ju . "
Àní sẹ́ , bí àwọn èèyàn tó wà nínú ayé Sátánì tilẹ̀ ń ṣe àìdáa sí wa nísinsìnyí , ó dá wa lójú hán - únhán - ún pé Ọlọ́run yóò ‘ ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ . ’
Ani se , bi awon eeyan to wa ninu aye Satani tile n se aidaa si wa nisinsinyi , o da wa loju han - unhan - un pe Olorun yoo ‘ se idajo ododo fun awon ayanfe re . ’
Fara wé òǹkọ̀wé Bíbélì kan tó gbàdúrà sí Ọlọ́run pé : “ Mú kí ojú mi kọjá lọ láìrí ohun tí kò ní láárí . ” — Sáàmù 119 : 37 .
Fara we onkowe Bibeli kan to gbadura si Olorun pe : " Mu ki oju mi koja lo lairi ohun ti ko ni laari . " -- Saamu 119 : 37 .
Rárá o , nítorí mímọ̀ pé ìwà wa ṣe pàtàkì lójú Ọlọ́run ń jẹ́ kí ayé wa túbọ̀ nítumọ̀ .
Rara o , nitori mimo pe iwa wa se pataki loju Olorun n je ki aye wa tubo nitumo .
Njẹ́ ẹ̀yin kò ha mọ̀ pé ọwọ́
Nje eyin ko ha mo pe owo
Àǹfààní ńlá ló jẹ́ fún wa láti máa fún Jèhófà , Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo , ní ọlá àti ògo tó tọ́ sí i ní gbogbo ọ̀nà ! — 1 Tím .
Anfaani nla lo je fun wa lati maa fun Jehofa , Eledaa ohun gbogbo , ni ola ati ogo to to si i ni gbogbo ona ! -- 1 Tim .
O nílò àkókò láti fi mọ ohun tó o fẹ́ àti ohun tí o kò fẹ́ àti láti ní ìrírí nípa ìgbésí ayé , èyí tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti yan ọkọ tàbí aya tó tẹ́ ẹ lọ́rùn .
O nilo akoko lati fi mo ohun to o fe ati ohun ti o ko fe ati lati ni iriri nipa igbesi aye , eyi to maa ran e lowo lati yan oko tabi aya to te e lorun .
Nínú apá àkọ́kọ́ , wọ́n to orúkọ gbogbo àwọn òǹkọ̀wé tí wọ́n fòfin de ìwé wọn , láìka ohun yòówù kí ìwé náà dá lé lórí sí .
Ninu apa akoko , won to oruko gbogbo awon onkowe ti won fofin de iwe won , laika ohun yoowu ki iwe naa da le lori si .
bẹ̀ẹ̀.
bee.
Tí ẹ bá fura pé ẹnì kan ti ní àmì àìsàn náà lára ńkọ́ ?
Ti e ba fura pe eni kan ti ni ami aisan naa lara nko ?
“Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹran pẹlu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ lọ máa woṣẹ́, tabi kí ẹ gba àjẹ́. Diut 18:10
“E ko gbodo je eran pelu eje re, bee ni e ko gbodo lo maa wose, tabi ki e gba aje. Diut 18:10
Ọpẹ́ ni fỌlọrun, nítorí pé ẹ̀yin tí ẹ̀ ń ṣẹrú ẹ̀ṣẹ̀ tẹ́lẹ̀ rí, ti wá ń fi tọkàntọkàn gba irú ẹ̀kọ́ tí a gbé kalẹ̀ níwájú yín.
Ope ni fOlorun, nitori pe eyin ti e n seru ese tele ri, ti wa n fi tokantokan gba iru eko ti a gbe kale niwaju yin.
Oríṣiríṣi ọ̀nà tó jọni lójú làwọn èèyàn ti gbà láti jẹ́ kí àwọn ọ̀rọ̀ inú Ìwé Mímọ́ wà nípamọ́ fún wa , títí kan kíka ọ̀rọ̀ tí wọ́n ti kọ òmíràn lé .
Orisirisi ona to joni loju lawon eeyan ti gba lati je ki awon oro inu Iwe Mimo wa nipamo fun wa , titi kan kika oro ti won ti ko omiran le .
Àwòrán yìí kì í ṣe àlá lásán o .
Aworan yii ki i se ala lasan o .
Wọ́n ti retí - retí , wọn ò tíì gbọ́ nǹkan kan di báa ti ń wí yìí o .
Won ti reti - reti , won o tii gbo nnkan kan di baa ti n wi yii o .
Téèyàn bá ṣàkọsílẹ̀ ìtọ́ni nípa irú ìtọ́jú ìṣègùn tó ń fẹ́ ṣáájú , ìyẹn máa ń jẹ́ káwọn èèyàn lè túbọ̀ bọ̀wọ̀ fáwọn ẹ̀tọ́ yẹn , kí wọ́n sì jẹ́ kí aláìsàn náà kú sílé rẹ̀ tàbí sílé ìwòsàn .
Teeyan ba sakosile itoni nipa iru itoju isegun to n fe saaju , iyen maa n je kawon eeyan le tubo bowo fawon eto yen , ki won si je ki alaisan naa ku sile re tabi sile iwosan .
▪ Ìgbà wo ni yíya àgùntàn àti ewúrẹ́ sọ́tọ̀ wáyé ? — October 15 , 1995 , ojú ìwé 18 sí 28 .
▪ Igba wo ni yiya aguntan ati ewure soto waye ? — October 15 , 1995 , oju iwe 18 si 28 .
Ẹlẹ́rìí náà bá Keith àti ìyàwó rẹ̀ pàdé ní ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà , ó sì wá rí i pé wọ́n ti di arákùnrin àti arábìnrin òun nípa tẹ̀mí .
Elerii naa ba Keith ati iyawo re pade ni opo odun leyin naa , o si wa ri i pe won ti di arakunrin ati arabinrin oun nipa temi .
▪ Máa Fọ̀rọ̀ Wọn Ro Ara Rẹ Wò .
▪ Maa Foro Won Ro Ara Re Wo .
18 May 2015.
18 May 2015.