cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
“Ohun ọ̀sìn kò ṣéé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú iṣẹ́ àgbẹ̀ lágbáyé." Bákan náà, Ọ̀mọ̀wé Adéọlá Ọdẹdínà tó ti fìgbà kan rí jẹ́ ọ̀gá àgbà pátá nílé ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Moshood Abiola, ìyẹn Mápoly tó wà nílùú Abeokuta fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé kò le sí wàhálà kankan láàrín iléeṣẹ́ tuntun yìí àti iléeṣẹ́ ìjọba tó ń rí sọ́rọ̀ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn..
bbc
yo
“Ohun ọ̀sìn kò ṣéé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nínú iṣẹ́ àgbẹ̀ lágbáyé." Bákan náà, Ọ̀mọ̀wé Adéọlá Ọdẹdínà tó ti fìgbà kan rí jẹ́ ọ̀gá àgbà pátá nílé ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Moshood Abiola, ìyẹn Mápoly tó wà nílùú Abeokuta fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé kò le sí wàhálà kankan láàrín iléeṣẹ́ tuntun yìí àti iléeṣẹ́ ìjọba tó ń rí sọ́rọ̀ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn.
bbc
yo
Ó ní “Tí a bá wò ó nígbà kan, abẹ́ iléeṣẹ́ tó ń rí sọ̀rọ̀ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn ni gbogbo iléeṣẹ́ yìí wà tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n tí ìjọba sọ pé kí wọ́n dá dúró báyìí..
bbc
yo
Ó ní “Tí a bá wò ó nígbà kan, abẹ́ iléeṣẹ́ tó ń rí sọ̀rọ̀ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn ni gbogbo iléeṣẹ́ yìí wà tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n tí ìjọba sọ pé kí wọ́n dá dúró báyìí.
bbc
yo
“Nígbà tí a gba òmìnira, iléeṣẹ́ àgbẹ̀ àti ọ̀gbìn nìkan ni òyìnbó fi sílẹ̀ fún wa.
bbc
yo
Lára àwọn ilese tó sì wà lábẹ́ rẹ̀ ní iléeṣẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ Ìgbò, ètò àyíká, okóòwò àti ìdásẹ̀sílẹ̀ àti àwọn míràn kò tó di pé ìjọba pín wọn sọ́tọ̀ọ̀tọ̀..
bbc
yo
Lára àwọn ilese tó sì wà lábẹ́ rẹ̀ ní iléeṣẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ Ìgbò, ètò àyíká, okóòwò àti ìdásẹ̀sílẹ̀ àti àwọn míràn kò tó di pé ìjọba pín wọn sọ́tọ̀ọ̀tọ̀.
bbc
yo
“Tí iléeṣẹ́ tó ń sọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn náà bá dá dúró, o máa tún jẹ́ kí iṣẹ́ pọ̀ ni, ojú a sì le ká wọn.".
bbc
yo
Bákan náà, ọ̀mọ̀wé Adeola odedínà to ti fìgbà kan rí jẹ́ ọ̀gá àgbà pátá nílé ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Moshood Abiola, ìyẹn MPoly tó wà nílùú Abeokuta fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé kò lè sí wàhálà kankan láàrín iléeṣẹ́ tuntun yìí àti iléeṣẹ́ ìjọba tó ń rí sọ́rọ̀ agbe àti ọ̀gbìn.
bbc
yo
“Tí iléeṣẹ́ tó ń sọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn náà bá dá dúró, ó máa tún jẹ́ kí iṣẹ́ pọ̀ ni, ojú a sì le kà wọ́n.” Síwájú síi nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa bí wàhálà àwọn àgbẹ̀ àti darandaran yóò ṣe dínkù, Ọ̀mọ̀wé Adéọlá jẹ́ kó di mímọ̀ pé ìpàdé àlàáfíà láàrín àwọn méjèèjì yìí ló le mú kí wàhálà náà dópin..
bbc
yo
“Tí iléeṣẹ́ tó ń sọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn náà bá dá dúró, ó máa tún jẹ́ kí iṣẹ́ pọ̀ ni, ojú a sì le kà wọ́n.” Síwájú síi nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa bí wàhálà àwọn àgbẹ̀ àti darandaran yóò ṣe dínkù, Ọ̀mọ̀wé Adéọlá jẹ́ kó di mímọ̀ pé ìpàdé àlàáfíà láàrín àwọn méjèèjì yìí ló lè mú kí wàhálà náà dópin.
bbc
yo
“Bi a bá yọwọ́ ti Òṣèlú kúrò, ki àwọn darandaran àti àgbẹ̀ joko ìpàdé lati bá ara wọn sọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bi oníṣòwò ti wọn kò gbọ́dọ̀ pa ara wọn lára..
bbc
yo
“Bí a bá yọwọ́ ti òṣèlú kúrò, kí àwọn darandaran ati àgbẹ̀ joko ìpàdé láti bá ara wọn sọ̀rọ̀ gẹ́gẹ́ bí oníṣòwò tí wọn kò gbọdọ̀ pa ara wọn lára.
bbc
yo
“Ìgbà míràn wà tó jẹ́ pé òṣèlú ló máa ń dá wàhálà yìí sílẹ̀.
bbc
yo
Kódà, láàrin inú ilé wa gan-an, aáwọ̀ máa ń wà, ṣugbọn a máa ń yanjú ẹ̀ ni, kò síbi tí kò sí aáwọ̀ ni.
bbc
yo
A ní láti yanjú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òwò ni, kìí ṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òṣèlú.".
bbc
yo
A ní láti yanjú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe ọwọ́ ni, kìí ṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òṣèlú.” Orísun àwòrán, aṣíwájú Bọ́lá Tinúbú/Facebook.
bbc
yo
Síwájú síi nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa bí wàhálà àwọn àgbẹ̀ àti darandaran yóò ṣe dínkù, Ọ̀mọ̀wé Adéọlá jẹ́ kó di mímọ̀ pé ìpàdé àlàáfíà láàrín àwọn méjèèjì yìí ló lè mú kí wàhálà náà dópin.
bbc
yo
A ní láti yanjú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òwò ni, kìí ṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òṣèlú.” Orísun àwòrán, aṣíwájú Bọ́lá Tinúbú/Facebook nígbà tóun náà ń sọ̀rọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n nípa nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀ Nàìjíríà, Ọlọ́runtóbi Olusegun.
bbc
yo
A ní láti yanjú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òwò ni, kìí ṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn tó ń ṣe òṣèlú.” Orísun àwòrán, aṣíwájú Bọ́lá Tinúbú/Facebook nígbà tóun náà ń sọ̀rọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n nípa nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀ Nàìjíríà, Ọlọ́runtóbi Olusegun “Bí a bá ní ká wò dáadáa, a lé ní nǹkan tí Nàìjíríà nílò lásìkò yìí ni.
bbc
yo
Ọ̀nà méjì ló pín sí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé lára àwọn ìdí tí ìjọba àpapọ̀ soi pé ó fa ìdásílẹ̀ iléeṣẹ́ yìí, gẹ́gẹ́ bí mo ṣe wò, ọ̀rọ̀ òṣèlú lásán ni mo kà á sí..
bbc
yo
Ọ̀nà méjì ló pín sí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé lára àwọn ìdí tí ìjọba àpapọ̀ soi pé ó fa ìdásílẹ̀ iléeṣẹ́ yìí, gẹ́gẹ́ bí mo ṣe wò, ọ̀rọ̀ òṣèlú lásán ni mo kà á sí.
bbc
yo
“Níbi tí Nàìjíríà dé dúró yìí, a ti nílò láti ní iléeṣẹ́ tó jẹ́ pé nǹkan ọ̀sìn nìkan ni wọ́n máa gbajúmọ̀.
bbc
yo
Ìdí ni pé bí ẹ bá lọ sí àwọn orílẹ̀èdè bíi Kenya tàbí Uganda, tí ẹ bá ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀, tí ẹ sì mẹ́nuba iṣẹ́ àgbẹ̀ ìgbàlódé, tí ẹ kò bá tètè sọ̀rọ̀ pẹ́ lórí ọkọ̀ ẹgẹ́ lé ń sọ nípa ẹ̀, ibi màlúù ni ọ̀kan tí wọ́n máa lọ..
bbc
yo
Orísun àwòrán, aṣíwájú Bọ́lá Tinúbú/Facebook nígbà tóun náà ń sọ̀rọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n nípa nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀ Nàìjíríà, Ọlọ́runtobi Olusegun "Bí a bá ní ka wò dáadáa, a lè ní nǹkan tí Nàìjíríà nílò lásìkò yìí ni.
bbc
yo
Ìdí ni pé bí ẹ bá lọ sí àwọn orílẹ̀èdè bíi Kẹ́ńyà tàbí Uganda, tí ẹ bá ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀, tí ẹ sì mẹ́nuba iṣẹ́ àgbẹ̀ ìgbàlódé, tí ẹ kò bá tètè sọ̀rọ̀ pẹ́ lórí ọkọ̀ ẹgẹ́ lé ń sọ nípa ẹ̀, ibi màlúù ni ọ̀kan tí wọ́n máa lọ.
bbc
yo
“Ohun tó gbajúmọ̀ lọ́dọ̀ ti wọn nìyẹn, ṣùgbọ́n tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ ìgbàlódé, nínú ọ̀kan ti wa, a ti ń rí àwòrán katakata nínú oko àgbàdo àti ègé, ohun tó sì wà lọ́kàn púpọ̀ ọmọ Nàìjíríà nìyẹn..
bbc
yo
Nígbà tóun náà ń sọ̀rọ̀, ọ̀jọ̀gbọ́n nípa nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, Ọlọ́runtobi olùṣẹ́gun "Bí a bá ní ká wò dáadáa, a lè ní nǹkan tí Nàìjíríà nílò lásìkò yìí ni.
bbc
yo
“Ohun tó gbajúmọ̀ lọ́dọ̀ ti wọn nìyẹn, ṣùgbọ́n tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ ìgbàlódé, nínú ọ̀kan ti wa, a ti ń rí àwòrán katakata nínú oko àgbàdo àti ègé, ohun tó sì wà lọ́kàn púpọ̀ ọmọ Nàìjíríà nìyẹn.
bbc
yo
“Láti ọdún pípẹ́ láti gbàgbé nípa ohun ọ̀sìn pátápátá.
bbc
yo
Láìpẹ́ yìí ni èmi àti ọ̀rẹ́ kan jọ ń sọ̀rọ̀ nípa ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran, tó sì lọ ń jẹ́ ìyàlẹ́nu fóun pé kò sí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ oníṣègùn nípa ẹran ọ̀sìn níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran ni Nàìjíríà..
bbc
yo
“Bí a bá ní ká wò dáadáa, a lè ní nǹkan tí Nàìjíríà nílò lásìkò yìí ni.
bbc
yo
Láìpẹ́ yìí ni èmi àti ọ̀rẹ́ kan jọ ń sọ̀rọ̀ nípa ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran, tó sì lọ ń jẹ́ ìyàlẹ́nu fòun pé kò sí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ oníṣègùn nípa ẹran ọ̀sìn níbi tí wọ́n ti ń pa ẹran ni Nàìjíríà.
bbc
yo
“Ẹni náà sọ pé oníṣègùn mẹ́ta péré ló wà ní ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran ní ìpínlẹ̀ osùn níbi tòun ti lọ sè Agùnbánirọ̀, èyí tí kò sì yẹ kó rí bẹ́ẹ̀.
bbc
yo
gbobo ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran ló yẹ kí àwọn dókítà ẹranko lọ máa bojútó, ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀..
bbc
yo
gbobo ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran ló yẹ kí àwọn dókítà ẹranko lọ máa bojútó, ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀.
bbc
yo
“Àwọn àgbẹ̀ ohun ọ̀sìn nílò ìrànlọ́wọ́, nítorí pé oríṣiríṣi ìròyìn ló ti ń lọ wí pé àwọn àgbẹ̀ ohun ọ̀sìn ti ń kó ìgbà wọlé.
bbc
yo
Bí ẹ bá sì gbé ọ̀rọ̀ yìí dé iléeṣẹ́ àgbẹ̀ ati ọ̀gbìn, wọ́n máa sọ pé wọ́n ṣì ń ṣàgbéyẹ̀wò rẹ̀ lọ́wọ́ ni, tí kò sì lè parí..
bbc
yo
Bí ẹ bá sì gbé ọ̀rọ̀ yìí dé iléeṣẹ́ àgbẹ̀ ati ọ̀gbìn, wọ́n máa sọ pé wọ́n ṣì ń ṣàgbéyẹ̀wò rẹ̀ lọ́wọ́ ni, tí kò sì lè parí.
bbc
yo
“Ní báyìí tí iléeṣẹ́ tó ń bojútó ohun ọ̀sìn ti wá, ó túmọ̀ sí pé gbogbo àwọn tí yóò máa ṣàkóso iléeṣẹ́ yìí ni wọ́n á jẹ àwọn tí òye iṣẹ́ náà yé, àti nípa bí nǹkan ṣe yẹ kó lọ lórí ọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn..
bbc
yo
“Ní báyìí tí iléeṣẹ́ tó ń bojútó ohun ọ̀sìn ti wá, ó túmọ̀ sí pé gbogbo àwọn tí yóò máa ṣàkóso iléeṣẹ́ yìí ni wọ́n á jẹ àwọn tí òye iṣẹ́ náà yé, àti nípa bí nǹkan ṣe yẹ kó lọ lórí ọ̀rọ̀ ohun ọ̀sìn.
bbc
yo
“Èyí yóo jẹ́ kí ètò ìsúná wà fún ohunkohun tí iléeṣẹ́ náà bá fẹ́ẹ̀ ṣe.
bbc
yo
Mo mọ̀ pé àyípadà rere máa wá nípa àwọn nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà láìpẹ́, ìyẹn bí wọ́n bá ṣe ojúṣe wọn dáadáa..
bbc
yo
Mo mọ̀ pé àyípadà rere máa wá nípa àwọn nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà láìpẹ́, ìyẹn bí wọ́n bá ṣe ojúṣe wọn dáadáa.
bbc
yo
“Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti ibi ìpàdé àpérò lórílẹ̀ Japan ni, lára àwọn tí a jọ pàdé níbẹ̀ jẹ́ kó yé wa pé ó ní iye tí ìjọba máa ń fún àwọn lórí wí pé wọ́n ń pèsè mílíìkì lásán, ó sì níye tí wọ́n ń ṣe jáde.
bbc
yo
“Bí màlúù kan bá kú lónìí, kò sí owó tí àgbẹ̀ yóò gbà lórí rẹ̀, àgbẹ̀ náà ló pàdánù.
bbc
yo
Tí mo bá gba mílíìkì, tí kò bá dára, ìpàdánù àgbẹ̀ lọ jẹ, kò sí nǹkan tí ìjọba fẹ́ ṣe sii..
bbc
yo
Tí mo bá gba mílíìkì, tí kò bá dára, ìpàdánù àgbẹ̀ lọ jẹ, kò sí nǹkan tí ìjọba fẹ́ ṣe sii.
bbc
yo
“Ṣugbọn tí iléeṣẹ́ yìí bá wà, gbogbo àwọn nǹkan wọnyi ni mo lérò wí pé wọ́n máa mójútó, tí ìlànà yóo sì wà.
bbc
yo
Ṣùgbọ́n síbẹ̀, ọ̀rọ̀ òṣèlú ni mo kà á sí láti mú ọkàn apá kan ní Nàìjíríà báble fúngbà díẹ̀.
bbc
yo
Èyí sì jẹ́ ọ̀kan lára ẹgbẹẹgbẹ̀rún wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ lásìkò yìí..
bbc
yo
Èyí sì jẹ́ ọ̀kan lára ẹgbẹẹgbẹ̀rún wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ lásìkò yìí.
bbc
yo
Orísun àwòrán, screenshot ojogbon Olusegun tesiwaju pe "Ǹjẹ́ a ri iléeṣẹ́ to ti yanjú ọ̀rọ̀ tí wọ́n gbé lé wọn lọ́wọ́ rí, ìbéèrè àkọ́kọ́ nìyẹn.
bbc
yo
Iléeṣẹ́ tó ń bojútó ètò ìlera ní Nàìjíríà, ṣé wọ́n ti bojútó gbogbo ètò ìlera tán nílé wa? Rárá! Wọ́n kàn máa ṣe ìwọ̀nba tí wọ́n lè ṣe ni..
bbc
yo
Iléeṣẹ́ tó ń bojútó ètò ìlera ní Nàìjíríà, ṣé wọ́n ti bojútó gbogbo ètò ìlera tán nílé wa? Rárá! Wọ́n kàn máa ṣe ìwọ̀nba tí wọ́n lè ṣe ni.
bbc
yo
“Ṣugbọn lórí èyí tí à ń sọ yìí, ó máa rọrùn díẹ̀ láti ṣe òdiwọ̀n ohun tí wọn ń ṣe ni.
bbc
yo
Ipa tí wọn ń kó la máa mọ̀ bí iṣẹ́ bá ṣe ń lọ lọ́dọọdún.
bbc
yo
Káàkiri àgbáyé, kò sí iléeṣẹ́ tó lè yanu ìṣòro patapata, ṣugbọn tó kàn máa mú àdínkù bá ìṣòro ọ̀hún lásán ni..
bbc
yo
Káàkiri àgbáyé, kò sí iléeṣẹ́ tó lè yanu ìṣòro patapata, ṣugbọn tó kàn máa mú àdínkù bá ìṣòro ọ̀hún lásán ni.
bbc
yo
“Tó bá jẹ́ iléeṣẹ́ yìí ni wọ́n máa ní kó ṣàkóso lórí wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ láàrín àgbẹ̀ àti darandaran, ó má rọrùn láti tètè béèrè lọ́wọ́ wọn nípa ipa tí wọ́n ti kó láàrín ọdún kan, ọdún méjì, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ..
bbc
yo
“Tó bá jẹ́ iléeṣẹ́ yìí ni wọ́n máa ní kó ṣàkóso lórí wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ láàrín àgbẹ̀ àti darandaran, ó má rọrùn láti tètè béèrè lọ́wọ́ wọn nípa ipa tí wọ́n ti kó láàrín ọdún kan, ọdún méjì, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ.
bbc
yo
“Ẹ má gbàgbé pé iléeṣẹ́ yìí kò níí jókòó sílùú àbùjá nìkan, wọ́n máa ní ẹ̀ka iléeṣẹ́ káàkiri ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan.
bbc
yo
Ohun tó jẹ ẹ̀mí lógún jùlọ ni ipa rere tí wọ́n máa kó lẹ́ka ètò ohun ọ̀sìn àti àgbẹ̀ ní Nàìjíríà nígbà tí iṣẹ́ bá bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.".
bbc
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n Olúṣẹ́gun tẹ̀síwájú pé "Ǹjẹ́ a rí iléeṣẹ́ tó ti yanjú ọ̀rọ̀ tí wọ́n gbé lé wọn lọ́wọ́ rí, ìbéèrè àkọ́kọ́ nìyẹn.
bbc
yo
Ohun tó jẹ ẹ̀mí lógún jùlọ ni ipa rere tí wọ́n máa kó lẹ́ka ètò ohun ọ̀sìn àti àgbẹ̀ ní Nàìjíríà nígbà tí iṣẹ́ bá bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.” Orísun àwòrán, Getty Images.
bbc
yo
Ohun tó jẹ ẹ̀mí lógún jùlọ ni ipa rere tí wọ́n máa kó lẹ́ka ètò ohun ọ̀sìn àti àgbẹ̀ ní Nàìjíríà nígbà tí iṣẹ́ bá bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.” Orísun Àwòrán, Getty Images Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kéde ìdásílẹ̀ ẹ̀ka Ìjọba tí yóò ma risi nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà láti lè fòpin àwọ tó ma ń wáyé láàrín àwọn àgbẹ̀ àti darandaran nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàívra..
bbc
yo
Ohun tó jẹ ẹ̀mí lógún jùlọ ni ipa rere tí wọ́n máa kó lẹ́ka ètò ohun ọ̀sìn àti àgbẹ̀ ní Nàìjíríà nígbà tí iṣẹ́ bá bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu.” Orísun Àwòrán, Getty Images Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kéde ìdásílẹ̀ ẹ̀ka Ìjọba tí yóò ma risi nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà láti lè fòpin àwọ tó ma ń wáyé láàrín àwọn àgbẹ̀ àti darandaran nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàírara.
bbc
yo
Ààrẹ buwọ̀lú ìdásílẹ̀ lọjọ́ Ìṣẹ́gun nígbà tó ń ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn Ìgbìmọ̀ Tó Ń risi Nǹkan Ọ̀sìn ní Ilé Ìjọba Nílùú Abuja..
bbc
yo
Ààrẹ buwọ̀lú ìdásílẹ̀ lọjọ́ ìṣègùn nígbà tó ń ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn Ìgbìmọ̀ Tó Ń risi Nǹkan Ọ̀sìn ní Ilé Ìjọba nílùú Àbújá.
bbc
yo
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni àwọ̀ ti bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn àgbẹ̀ ati darandaran ṣugbọn àárẹ̀ ni òun gbàgbọ́ pé ìdásílẹ̀ ẹ̀ka yìí yóo yanjú gbogbo ìṣòro náà..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kéde ìdásílẹ̀ ẹ̀ka Ìjọba tí yóò ma risi nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà láti lè fòpin àwọ tó ma ń wáyé láàrín àwọn àgbẹ̀ àti darandaran nǹkan ọ̀sìn lórílẹ̀èdè Nàíra.
bbc
yo
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni àwọ̀ ti bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn àgbẹ̀ ati darandaran ṣugbọn àárẹ̀ ni òun gbàgbọ́ pé ìdásílẹ̀ ẹ̀ka yìí yóo yanjú gbogbo ìṣòro náà.
bbc
yo
“Ta ló ni ọ̀nà àbáyọ jiná? Mo ní, rárá, ọ̀nà àbáyọ ti dé.
bbc
yo
Ọ̀pọ̀ yín ni ẹ ní ìrírí tó dára, tí ẹ sì fẹ́ kí orílẹ̀èdè gbọ́rọ̀ sí,“ ààrẹ sọ..
bbc
yo
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kede idasilẹ ẹka Ijoba ti yoo ma risi nǹkan ọsin lórílẹ̀ Naijiria lati le fopin awo to ma n waye laarin awọn agbe ati darandaran nnkan Ajeede lórílẹ̀ede |ra.
bbc
yo
Ọ̀pọ̀ yín ni ẹ ní ìrírí tó dára, tí ẹ sì fẹ́ kí orílẹ̀èdè gbọ́rọ̀ sí,“ ààrẹ sọ.
bbc
yo
“Láti jẹ́ kí Nàìjíríà jẹ́ àǹfàní ètò ọ̀sìn, a ti rí ọ̀nà àbáyọ tí yóò ṣe àǹfàní láti tán gbogbo ìṣòro tí a ń dojúkọ láti ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn, tí mo sì gbàgbọ́ pé ìdàgbàsókè ti dẹ ṣowó wa báyìí.".
bbc
yo
“Láti jẹ́ kí Nàìjíríà jẹ́ àǹfàní ètò ọ̀sìn, a ti rí ọ̀nà àbáyọ tí yóò ṣe àǹfàní láti tán gbogbo ìṣòro tí a ń dojúkọ láti ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn, tí mo sì gbàgbọ́ pé ìdàgbàsókè ti dẹ ṣowó wa báyìí." Pẹ̀lú ìgbésẹ̀ yìí, ààrẹ ní Nàìjíríà yóò tẹ̀síwájú láti ṣe ohun tó tọ́ láti rí pé ààbò wà fún nǹkan ọ̀gbìn tó ń wá láti oko..
bbc
yo
“Láti jẹ́ kí Nàìjíríà jẹ́ àǹfàní ètò ọ̀sìn, a ti rí ọ̀nà àbáyọ tí yóò ṣe àǹfàní láti tán gbogbo ìṣòro tí a ń dojúkọ láti ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn, tí mo sì gbàgbọ́ pé ìdàgbàsókè ti dẹ ṣowó wa báyìí." Pẹ̀lú ìgbésẹ̀ yìí, ààrẹ ní Nàìjíríà yóò tẹ̀síwájú láti ṣe ohun tó tọ́ láti rí pé ààbò wà fún nǹkan ọ̀gbìn tó ń wá láti oko.
bbc
yo
Bákan náà ni Ààrẹ ní òun ṣetán láti pèsè owó fún ríra ilẹ̀ láti rí pé ìbágbépọ̀ àlàáfíà wà láàrín àgbẹ̀ àti àgbẹ̀ nǹkan ọ̀sìn..
bbc
yo
Bákan náà ni Ààrẹ ní òun ṣetán láti pèsè owó fún ríra ilẹ̀ láti rí pé ìbágbépọ̀ àlàáfíà wà láàrín àgbẹ̀ àti àgbẹ̀ nǹkan ọ̀sìn.
bbc
yo
Ààrẹ Bola Tinubu ni yoo jẹ Alaga Igbimọ naa, ti Alaga ajo elétò idibo tẹlẹ lórílẹ̀ Nàìjíríà, Attahiru Jega yoo jẹ Igbakeji..
bbc
yo
Ààrẹ Bola Tinubu ni yoo jẹ Alaga igbimọ naa, ti Alaga ajo elétò idibo tẹlẹ lórílẹ̀ Nàìjíríà, Attahiru Jega yoo jẹ Igbakeji.
bbc
yo
Ìgbìmọ̀ yìí ni yóò pèsè ọ̀nà àbáyọ sí bí ìbágbépọ̀ àlàáfíà yóò ṣe wà láàrín àwọn àgbẹ̀ àti darandaran, rírí dájú pé ètò ààbò náà wà, àǹfàní fún ètò ọrọ̀ ajé àti fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà..
bbc
yo
Pẹ̀lú ìgbésẹ̀ yìí, Ààrẹ ni Nàìjíríà yóò tẹ̀síwájú láti ṣe ohun tó tọ́ láti ri pé ààbò wà fún nǹkan ọ̀gbìn tó ń wá láti oko.
bbc
yo
Ìgbìmọ̀ yìí ni yóò pèsè ọ̀nà àbáyọ sí bí ìbágbépọ̀ àlàáfíà yóò ṣe wà láàrín àwọn àgbẹ̀ àti darandaran, rírí dájú pé ètò ààbò náà wà, ànfàní fún ètò ọrọ̀ ajé àti fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà.
bbc
yo
Ìkéde yìí ń wáyé lẹ́yìn oṣù mẹ́wàá tí Ààrẹ buwọ̀lú ìdásílẹ̀ Ìgbìmọ̀ Iléeṣẹ́ Ààrẹ tó tán ìṣòro àwọn àgbẹ̀ àti darandaran, ti bí ètò ọ̀sìn yóò gboro sí..
bbc
yo
Ìkéde yìí ń wáyé lẹ́yìn oṣù mẹ́wàá tí Ààrẹ buwọ̀lú ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ iléeṣẹ́ Ààrẹ tó tán ìṣòro àwọn àgbẹ̀ àti darandaran, ti bí ètò ọ̀sìn yóò gboro sí.
bbc
yo
Ààrẹ dá ìgbìmọ̀ náà sílẹ̀ lẹ́yìn tó àbọ̀ ìwádìí láti bí Àpérò ètò Ọ̀sìn , tí alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Abdullahi Gandújẹ̀ jẹ́ Alága fún, tí wọ́n sì pe ọ̀nà àbáyọ mọ́kànlélógún, pàá dídá ẹ̀ka ètò ọ̀sin sílẹ̀ fún Ààrẹ Bólá Tinúbú..
bbc
yo
Ààrẹ Bola Tinubu ni yoo jẹ Alaga Igbimọ naa, ti Alaga ajo elétò idibo tẹlẹ lórílẹ̀ Naijiria, Attahiru Jega yoo jẹ Igbakeji.
bbc
yo
Ààrẹ dá ìgbìmọ̀ náà sílẹ̀ lẹ́yìn tó àbọ̀ ìwádìí láti bí Àpérò ètò Ọ̀sìn , tí alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Abdullahi Gandújẹ̀ jẹ́ Alága fún, tí wọ́n sì pe ọ̀nà àbáyọ mọ́kànlélógún, pàá dídá ẹ̀ka ètò ọ̀sin sílẹ̀ fún Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images Àjọ Àgbáyé un ti ṣèkìlọ̀ pé èèyàn ló ni ọgọ́rin lọ́mílò tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà ni ó ṣeéṣe kí wọ́n kojú ẹbí ní ọdún 2030.
bbc
yo
Ẹ̀ka tó ń rí oúnjẹ àti ọ̀gbìn ní àjọ àgbáyé ún ló gbé ìwádìí yìí kalẹ̀ láti ṣe àfihàn bí nǹkan yóò ṣe rí ní lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ní ọjọ́ ọ̀la.
bbc
yo
Bákan ni Mdd tún késí orílẹ̀èdè Nàìjíríà láti wá ojutu sí ìṣòro ojú ọjọ́, ìṣòro kòkòrò àti àwọn nǹkan míì tó ń dùnkòkò mọ́ ètò ọ̀gbìn lórílẹ̀èdè Nàìjíríà.
bbc
yo
“Ìjọba orílẹ̀èdè Nàìjíríà pẹ̀lú àjọṣepọ̀ àwọn tí ọ̀rọ̀ kan, ti gbé ìwádìí dìde lórí ètò ọ̀gbìn àti oúnjẹ.
bbc
yo
Àbọ̀ ìwádìí náà ló mú ìbẹ̀rù dání nítorí ó lé ní èèyàn Milonu méjìléọgọrin tí yóò kojú ẹbí tó bá di ọdún 2030,” Taófikaq Braaragu ṣàlàyé fún àwọn akọ̀ròyìn nílùú Àbújá..
bbc
yo
Àjọ àgbàyé un ti ṣèkìlọ̀ pé èèyàn ló ni ọgọ́rin Mílònu tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà ni ó ṣeéṣe kí wọ́n kojú ẹbí ní ọdún 2030.
bbc
yo
Àbọ̀ ìwádìí náà ló mú ìbẹ̀rù dání nítorí ó lé ní èèyàn Milonu méjìléọgọrin tí yóò kojú ẹbí tó bá di ọdún 2030,” Taófikaq Bratyl ṣàlàyé fún àwọn akọ̀ròyìn nílùú Àbújá.
bbc
yo
Ó tẹ̀síwájú pé ìṣòro oúnjẹ tí a ní lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ni ó tan mọ́ kùdìẹ̀kudiẹ ojú ọjọ́ àti bí àwọn kòkòrò ṣe ń fa ọ̀pọ̀ ìjàmbá tó ń wáyé ní ẹ̀ka ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà..
bbc
yo
Ó tẹ̀síwájú pé ìṣòro oúnjẹ tí a ní lórílẹ̀èdè Nàìjíríà ni ó tan mọ́ kùdìẹ̀kudiẹ ojú ọjọ́ àti bí àwọn kòkòrò ṣe ń fa ọ̀pọ̀ ìjàmbá tó ń wáyé ní ẹ̀ka ọ̀gbìn lórílẹ̀ Nàìjíríà.
bbc
yo