sentence1
stringlengths
3
1.7k
sentence2
stringlengths
3
1.73k
lang
stringclasses
4 values
this movie has to be the most depressing romantic comedy we have ever seen.
Eré yìí ní láti jẹ́eré ìfẹ́ apanilẹ̀rin tí kò dùn tí a ti wò rí.
en400-yo400
Probably the worst acting ever in a movie which seems to be made with enough money.
Eléyìí ni yóò fẹ́ jẹ́ iṣẹ́ eré sinimá tí ó burú jù bó tilẹ̀ jé wípé owó tí ó tó ni wón fi sé é.
en400-yo400
Way too slow. What a waste of time.
Ó ti falẹ̀ jù. Ìf'àkókó ṣòfò ni
en400-yo400
I cant believe I spent 2 hours watching this movie
Ojú gbà mí tì pé mo fi wákàtí méjì mọ eré yìí
en400-yo400
i really don’t like this movie
N kò fi bẹ́ẹ̀ gba ti sinimá yìí jàre.
en400-yo400
PLOT IS ALMOST EMPTY.
Eré nàa fẹ́ẹ̀jẹ́ kòròfo
en400-yo400
Weak dialogue, amateurish battle scenes.
Ọ̀rọ̀ sísọ wọn kò kún ojú òsùwọ́n, àwọn ogun tí wọ́n jà dà bíi ti àwọn tí ó sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ isẹ́ tíátà ní kíkọ.
en400-yo400
From poor directing, to crap story; questionable acting to illogicality; shallow sceenwriting to bad editing..
Láti ìdarí tí kò da, dé ìtàn ti kò dùn, ó kún fún àìlọ́pọlọ àti àìláròjinlẹ̀
en400-yo400
This movie is ugly.
Eré náà burẹ́wà
en400-yo400
Asides from being terribly predictable and featuring generally below average acting, it is plagued by a be-fumbling series of subpar attempts at recreating worn out crime caper staples.
Yàtọ̀ sí pé èniyàn lè sọ oun tó ṣẹlẹ̀ ni ú eré náà àti àwọn Òṣeré tí kò kún ojú òṣùwọ̀n, òkun fún àwọn àwí_túńwí asán.
en400-yo400
I hate how this movie is titled.
Mo kórira bí wọ́n ṣe fún eré yí ní àkọlé.
en400-yo400
Bland and dreary, 'Efunsetan Aniwura' is an exposé in gratuitously lazy and painfully appalling story-telling.
Òfúútù fẹ́ẹ́tẹ̀, áásà tí kò ní kánún.. . Ẹ̀FÚNSETÁN ANÍWÚRÀ jẹ́ àfihàn ìṣe ìmẹ́lẹ́ àti ọ̀nà ìgbà sọ ìtàn tí ó dun’ni jọjọ
en400-yo400
I am livid
Inú ń bí mi gidigidi.
en400-yo400
THE LACK OF LANDSCAPE POSTERS FOR NOLLYWOOD FILMS
Àìsí àwọn ìwé àlẹ̀ mọ́ ògiri oní ìdábùú lẹ́lẹ́gbẹ̀ẹ́ fún àwọn fíìmù Nọ́líwuùdù.
en400-yo400
ABSOLUTE RUBBISH
Ósi parakutu
en400-yo400
this film promised so much but turned out to be gut wrenching ridiculous. Rubbish!!
Eré yìí mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrètí dání ṣùgbọ́n ó padà di oun tí ó ń múnú bíni púpọ̀.
en400-yo400
They seriously use smash bro’s title cards to introduce the characters...
Nítorí wọ́n lọ bro orí ọ̀rọ̀ láti fi ṣe ìfihàn àwọn ẹ̀dá...
en400-yo400
The movie seemed generally flat and draggy though out.
Fíìmù náà dàbí ẹnipé gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ ti wà ní fífà dé ìparí
en400-yo400
It promised laughter, but the comedy was minimal and elicited smiles rather than the hearty laughter you expect when you go to the cinema for a comedy.
Ó ṣe ìlérí ẹ̀rín, ṣùgbọ́n àwàdà jẹ́ ìwọ̀nba àti àwọn ẹ̀rin músẹ́ dípò ẹ̀rin ahun tí ó nírètí nígbàtí ó lọ sí sinimá fún àwàdà kan.
en400-yo400
Abigail isn't very good, the bad guy is a bit of a moustache twister, and they figured out that it sucks for black people to go back in time
Ábígẹ́lì kò dára tó bẹ́ẹ̀ náà, ẹni búburú ibẹ̀ jẹ́ asorun iwájú pọ̀ mọ́ tí ìpàkọ́. Wọ́n tún wá padà ríi wípé kò dára fún àwọn Adúláwò láti máa ka ọwọ́ aago padà sẹ́yìn.
en400-yo400
The lead female role a huge disappointment.
Ipò asíwájú obìnrin tó ga jù jẹ́ ìjákulẹ̀
en400-yo400
The ending was the only enjoyable part of this for me. Good for her.
ìparí rẹ nìkan ni ó padà du fún mi. Ó da fún ọ.
en400-yo400
A travesty. . This is a disgrace and an awful disservice to CNA. Shame on this "film".
Ìdójútì gbáà ni ètí jẹ́. . Kódà, ó ta àbùkù bá CNA.
en400-yo400
A Trainwreck of a movie. 90s minutes of dissapointing Sound editing and acting.
Ọ̀nà ṣe ère náà. Ìsẹ́jú àádọ̀rún tí ìjánikulẹ̀ ohun àgbéyèwo àti ṣíṣe ere
en400-yo400
confused. . Was this what a good movie looked like in Africa in 2012? If so then ... it was great! I have to wonder (in that case) if it's gotten any better in 2021?.
Ó ti dàrú mọ́ mi lójú o.. . Ṣé oun tí wọ́n pè ní sinimá gidi nílẹ̀ Adúláwọ lọ́dún 2012 rèé? Tí ó bá jẹ́ bẹ̀ẹ̀, ó dára! Mo wá ń rò ó wò pé ṣé ó ti dára ju ti tẹ́lẹ̀ lọ ní ọdún un 2021 bí?
en400-yo400
. Knock Out Blessing' is an utterly useless movie that ought not to have been made, or at least not released to the public. Rubbish!
Knock Out Blessing' jẹ́ eré tí kò ní ìwúlò rárá, kódà kò yẹ kí wọn gbe jáde. Òṣì.
en400-yo400
Unnecessarily long. . For me,
Gígùnjù tí kò wúlò
en400-yo400
for amateur actors that also had no direction from Akinropo. The sound was bad, probably from the lack of boom mics.
Fún àwọn òsèré tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ tí ó tún ní kò sí ìtọ́sọ́nà láti Akinrópò. Ohùn náà burú, bóyá láti àìní àwọn ariwo gbohùngbohùn.
en400-yo400
Suga Suga has too many eye rolling scenes that eventually ended in an anticlimactic resolution of a weak conflict.
Súgà Súgà ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwòye yíyí ojú tí ó parí ní ìparí ní ìpinnu apanirun tí rògbòdìyàn aláìlágbara.
en400-yo400
Dishearteningly, Enitan's transition from lost soul to a scholar and now an artist gets shoved into the final minutes left over after all the bleakness.
ìbànújẹ ọkàn, ìyípadà Ẹniìtàn láti ẹ̀mí tí ó sọnù sí ọ̀mọ̀wé kan àti ní báyì òṣèré kan ti lọ sínú àwọn ìṣẹ́jú ìkẹhìn tí ó kù lẹ́hìn gbogbo àìbalẹ̀ náà.
en400-yo400
My first Nigerian movie. . . . For the past several years, I have come across a number of reports telling about how the country of Nigeria has a successful domestic film industry. While that fact definitely intrigued me, I was unable to find any Nigerian movies available for me to look at until I stumbled upon this one on Netflix. To be honest, I was expecting something pretty crudely made, and to a large degree this is true. While there are some pretty good composed shots and/or direction that indicate that at times some real effort was being made by the filmmakers, the movie has far more shortcomings. The cinematography is unimpressive, there's very little in the way of production values, and the acting by many of the performers is amateurish. Actually, I might have been able to forgive all that had the movie's biggest problem did not exist, that being that it's far too long (121 minutes in length) and far too slowly paced. This is a story that really needed to be cut down either at the script stage or when the footage was being edited. There is a twist towards the end that's a little interesting (despite my ability to somewhat predict it before it unfolded), but it's too little and too late to make it worth sitting through a story that's too long and too slow. Still, if you have heard of Nigerian cinema and are curious about experiencing a sample of it, I've just told you of one possible accessible choice.
Ere ilẹ̀ Nàìjíríà àgbéléwò mi àkọ́kọ́ . . Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn, mo ti ṣe alábàápàdé ọ̀pọ̀lọpọ̀ èsì àti ìròyìn tó ń sọ nípa pé Nàìjíríà tí ni ile ìṣe tó n sàgbéjádé èré àgbéléwò. Bí ó tilè je pé èyí wúmi lórí, n kò rí eré ilé̩ Nàìjíríà kankan wo àfi ìgbà tí mo kàn sàdéédé rí èyí lórí Netflix. Lóòótọ́, nǹkan ti mò ń retí ni mo rí. Mo rí àwọn ibi tí w̩o̩n kó ṣe dáadáa látàrí àìsí irinsé̩ tó múnádóko. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ibi kọ̀ọ̀kan wà tí wọ́n ṣe dáadáa ati ìdarí tó tókasí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan ni àwọn osere ṣe, ère yìí ni àwọn kùdìè̩kudie̩ tó pò̩. Abala àwòrán yíya kò dára tó bẹ́ẹ̀ sì ni ère sise àwọn òs̩èré kò fi wọ́n hàn bí akó̩s̩é̩mo̩s̩é̩. . . Lóòótọ́, ǹ bá tilè̩ ní kí n fojú fò gbogbo àwọn kùdìè̩kudie̩ yìí ká sọ pé wàhálà ńlá tí ere yìí ni kò sí nibẹ. Ère yìí tí gùn ju (ìsé̩jú mó̩kànléló̩gó̩fà) bẹẹ si ni o ti fà nílè ju. Ó yẹ kí wọ́n gé ìtàn yìí kúrú yálà nígbà tí wọ́n ń kọ́ ọ ní tàbí nígbà tí wọ́n ń ṣe àgbéyè wo rẹ. Ibikan wá ní ibi ìparí rẹ tó wú ni lórí bí ó tilè̩ jé̩ pe mo wòye rẹ̩̀ kì ó tó ṣẹlẹ̀, ṣùgbọ́n kò pẹ́ rárá àti pé ìgbéjáde abala yìí ti pé̩ jù láti yí àwọn ènìyàn lọ́kàn padà nipa ere tó gùn tó sì tún fà nílè̩. Síbẹ̀ síbẹ̀ tí ó bá ti gbó̩ nípa Sinima ilé Nàìjíríà tí ó sì tún ń wù ọ láti ni ìrírí rẹ̀, a jẹ́ pé mò ti fi ìkan hàn ọ́.
en400-yo400
Unfortunately, we can't bear cowboy pistols, space guns, cut & sow costumes, annoyingly talentless filming and unnecessary long form remembrance ceremonies for already shown footage all buttered up with ridiculously unintelligent revelations of supposed-to-be shockers that were apparent from the beginning.
Láìlóríre, a ò lá fara dàa ìbọn Cowboy, ìbọn àlàfo, asoí wón ranrí wọ́n fi dábírà, eré tíwónse tí ó bí yàn nínù rí kòlébùn ríkòsí se pàtàkì, ayẹyẹ rí wón fi rántí eré tí wọ́n tí fi hàn tẹ́lẹ̀ tí wọ́n kójo pọ̀ tí kòsì nítumọ̀ láti bèrè
en400-yo400
Unfortunately, the film is often stately and sluggish with some very daytime-soapy moments of emotional revelation.
Ó n ṣe ní àánú, fíìmù náà nígbàgbogbo jẹ́ dáradàra àti onílọ́ra pẹ̀lú díẹ̀ nínú àwọn àkókò ọ̀ṣẹ̀ ọ̀sán púpọ̀ ti ìfihàn ẹ̀dùn.
en400-yo400
The movie wasn't great, a bit of overreaching of the actors (maybe over-directed?) but the context was great.
Eré náà ò dára, àṣejù díẹ̀ lát'ọ̀dọ̀ àwọn òṣèré (bóyá ìdarí tí pọ̀jù) sùgbón lílò rẹ̀ dára.
en400-yo400
Once Upon A Night' is a dud.
once upon a night' jẹ ọun tíkò níyì
en400-yo400
As it is, you get no sense of place or character because too much has to be glossed over to fit it all in.
bó sewà, kò láyè tàbí ìwà torí aní làti se oun púpọ̀ kóbalè wọlé tán
en400-yo400
This movie is too boring for cinema.
Fíìmù yìí jẹ́ aláìdùn púpọ̀ fún sinimá.
en400-yo400
bad
Kò dára
en400-yo400
We call it a kidnap- Held hostage for fifty odd minutes, we were forced on an excursion of the resort grounds, Not recommended.
apeè ní ajínigbé nínú àhámọ́ fun odidi àádọ́ta ìséjú, wọ́n fi tipátipá jẹ́ kalọ sí ìrìn àjò asegbyinti, àìfọwọsí
en400-yo400
This lion didn't have much of a roar. Did someone send their failed Netflix pilot script to Nigeria like it was the losing Super Bowl team's t-shirt?
Kìnnìún yìí kò lè bú ramúramù tó.. . Ṣé ẹnìkan fi ìtàn eré Netflix wọn tó ti fìdí rẹmı ṣòwò sì Nàìjíríà ni? Àfi bíi aṣọ àwọ̀díje ẹgbẹ́ t’ó fìdí rẹmı nínú àșekágbá Super Bowl ni.
en400-yo400
Forceful story-telling and embarrassingly bad acting are the hallmarks of this shabby pretender - Might sound weird but; this flick is like a counterfeit of 'Isoken'.
Ì fagídí sọ ìtàn àti ìṣọwọ́ ṣeré tó ti ni l’ójú ni àwọn ǹkan tí ó jẹ́ àdámọ̀ ère rádaràda tí ń pe ara rẹ̀ ní ohun tí kò jẹ́ yìí. Ó lè má rọrùn fún yín láti gbà ṣùgbọ́n eré yìí dàbí ayédèrú Isoken.
en400-yo400
Dumb movie. . This movie is a joke.
eré tíkò ní ìtumọ̀. . àwàdà leré yí
en400-yo400
Diabolically bad!. . This is realistically the worst movie I've ever seen in my life!
Ẹ̀bu burúkú !. . Èyí ni Eré oníṣe burúkú tí mo ti rírí ní Ilé ayé mi!
en400-yo400
Action sequences weren't bad and its heart was in the right place, but quite painful to watch in places.
Àkójọpe Ere náà ki ṣe èyí tó burú. Ọkàn rẹ sì wá ní ibi tó dáa gangan, ṣùgbón óṣeni láànú láti wo ni ọ̀nà oríṣiríṣi
en400-yo400
Though the cinematography looks professional, don't let this film fool you. It's a disaster.
Bíotìlẹ̀jẹ́pé ere náà dá bí ti akọ́ṣẹ́mọsẹ́, má jẹ́ kí ó mú ọ́ bíi òmùgọ̀. Ibi ni
en400-yo400
No head, no tail, bad script, absolute waste of time and expensive rubbish. Movie was such a pain to watch. I highly do not recommend.
Kò s'órí kò s'írù, ìtàn burúkú àti ìranù tó wọ́n. Ó tilẹ̀ le láti wò. Nkò lè ròyin rẹ̀ fun elòmíràn
en400-yo400
their star quality is lacking in this movie
dídára ìràwọ̀ wọn kò ní nínú fíìmù yìí
en400-yo400
lolz
Ẹ̀rín pa mí.
en400-yo400
Verdict: Not recommended. 'Charmed' is not charming.
nkan àìtọ́. rẹwà. kò rẹwà
en400-yo400
So disapppointed.. . Some acting moments from main actors (king and Amina), but the supporting actor (Maladi), hard to tell if he is comic relief because his role should be serious.
Ojú gbà mí tì.. . Àwọn òsèré tó kópa nínú eré yìí rí àwọn ibi kọ̀ọ̀kan se dáadáa nibe paapaa, Kabiyesi ati Amina, sugbon awon osere to sugba won(Maladi),ko tile yeni boya won kan ni ki o maa pa wa lerin ni nitori o ye ki o fi ara si ju bi o ti se lo.
en400-yo400
Rubbish! Not recommended for anybody. Not even children. Very irritating movie.
Oshi! Nkò lè sọ fún ẹnikẹ́ni nípa rẹ̀. Kò dá b'ó jẹ́ ọmọdé. Ère náà rínílára.
en400-yo400
Hands down one of the worst movies I’ve ever seen
Láì sí àní-àní, eléyìí wà lára àwọn sinimá tó burú jù tí mo ti wó.
en400-yo400
Worst remake. . There was poor directing at the beginning during Ahannas flashbacks when he witnessed a man being set ablaze.
Sinimá àtúngbékalẹ̀ tí kò dára rárá.. . Ní ìbẹ̀rẹ̀ eré yìí, ní ibití Áhánásì ti ń rántí ẹni tí wọ́n da iná sun, bí wọn ṣe darí ibẹ̀yẹn kò dára tó.
en400-yo400
Rubbish. . . . One more piece of garbage from NETFLIX. Period !!
Rádaràda. . ohun òṣì kan sìì láti ọwọ́ NETFLIX ní àkókò yìí.
en400-yo400
Extremely flawed
Gbogbo ọ̀nà ni ó fi mẹ́hẹ̀e
en400-yo400
I skimmed this. no way i’m watching the whole thing
Mo fo èyí. Kò sí ọna ti mo lè fi wọ gbogbo kiní yìí
en400-yo400
you will regret wasting your time watching this movie
Ó má kàbámọ́wípé o wo eré yìí.
en400-yo400
Poor
Tí Kò dára
en400-yo400
Excessively basic.
Ìpìlẹ̀ tí ó pọ̀jù.
en400-yo400
The Millions' is essentially a shameless wholesale theft of 'Ocean's film series' scripts; we were not impressed.
Àwọn Mílíọ̀nù' jẹ́ pàtàkì jíjá òsùnwọ̀n tí kò ní ìtìjú tí àwọn ìwé àfọwọ́kọ 'Ocean's film series'; ṣùgbọ́n kò wú wa lórí rárá.
en400-yo400
Gbarada' is a typical Idumota "Yoruba film" with all the craziness that come with that sub-section of Nollywood.
Gbàràdá jé ìjìnlẹ̀ eré yorùbá ìdúmọ̀tà pẹ̀lú gbogbo ìwà wèrè tó bá abala nollywood yẹn wá.
en400-yo400
Holy one of Israel!. . What did Genevieve think she just did? A movie? This is corruption in the highest. The writers are quack.
Ẹni mímọ́ Isrélì!. . Kínni Genevieve rò pé òún ṣe? Eré? Ìwà ìbàjẹ́ tó gajù ni èyí.. . Olùkọ'tàn naa kò dáa tó.
en400-yo400
the worst movie production ever
Àsopò eré tí ó tíi burú jù.
en400-yo400
Just Crap
Òṣì lásán
en400-yo400
Special Jollof' is yet another cold turkey from Nollywood in Diaspora. And as usual; it is highlighted by a yéyé story and a plethora of half hearted acting performances. There's nothing to see here. It's a total waste of money and time.
"Special Jollof" tún jé̩ eré mìíràn tí àwọn òs̩èré Nollywood tó wà ní Turkey ṣe ṣùgbọ́n tí kò gbádùn rárá. Eré yeye ni a fi ṣe bẹ̩́ẹ̩̀ ni ó kún fún onírúurú àwọn iṣé tí kò kún ojú òṣùwọ̀n. Kò sí ń kankan nínú eré yìí. Ìfàkókò àtowó ṣòfò lásán ni.
en400-yo400
I can confidently say that Luna taking a shit is a way more engaging story than chief daddy 2.
Gbogbo ẹnu ni mo lè fi sọ wípé, bi Lúnà ṣe gba ìgbàkugà gan-an, ìtàn tó wọ̀ ni lára ju Chief Daddy apá kejì lọ.
en400-yo400
i did not realise how many plane crashes there were in nigeria, and this film came out five days
Mí o mọ iye ìjàmbá ọkọ̀ Òfurufú ti o waye ni orilẹ èdè Nàíjíríà ,bẹ́ẹ̀ni Ere to jade ni ọjọ́ márùn-ún .
en400-yo400
This Movie Would Have Done Better If Funded More ,
Fíìmù náà kò bá ti dára tí ó bá jẹ wípé wọ́n ná owó síi dáadáa
en400-yo400
With no modulating direction and no subtlety, this is a long, hard slog that will best be appreciated by friends and family of those in the cast and crew
Láìsí ìtọ́sọ́nà àti ìtumọ̀, eléèyí jẹ́ kan tó gùn , tó le tí yóò ti ò fi le dára níwájú àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí tí àwọn tí olùdarí àti àwọn òṣèré.
en400-yo400
Not worth your time
Kò yẹ̩ láti gba àkókò rẹ
en400-yo400
Utter rubbish. . It's very rare that I give up on a film, I couldn't finish this, gave up after 30mins. Don't waste your time.
Réderède gbáà!. . Kò wọ́ pọ̀ kí n pa sinimá tì, ṣùgbọ́n, n kò le wo èyí tán. Lẹ́yìn ọgbọ̀n ìṣẹ́jú ni mo dáa dúró.. . Má fi àkókò rẹ sòfò.
en400-yo400
ultimately dampening the film overall for what could have been an even stronger, hard-hitting and poignant emotional roller coaster.
Fún ohun tí kò bá jẹ́ sinimá tó lágbára, tí ọ̀rọ̀ ìfẹ́ inú rẹ̀ kàn ń ṣubú lé ara wọn, ó ṣeni láàánú pé wọ́n kàn bú omi rín ni.
en400-yo400
Unfortunately lack of attention to detail didn't stop with the aforementioned examples.
Ó tini lójú pé àìle ṣe iṣẹ́ à ṣe parí lórí ohun gbogbo kò tán sì àwọn àpẹrẹ tí a ti mú ẹnu bà tẹ́lẹ̀.
en400-yo400
The Wait is full of stars, but it does not shine bright. It is like tasting a glass of wine that has not fully developed, perhaps, made with unripe grapes.
Ìdúró náà kún fún àwọn ìràwọ̀, ṣúgbọ̀n kò tan ìmọ́lẹ̀. Ńṣe ló dà bí ìgbà tí wọ́n ń tọ́jú wáìnì kan tí kò tíì dàgbà, bóyá tí wọ́n fi èso àjàrà tí kò tíì pọ́n ṣe.
en400-yo400
This movie is so cheesy.
Eré yí kò kún tó.
en400-yo400
this is an extremely boring and terrible film
Fíìmù yìí ó dáa rárá bẹ́ẹ̀ sì ni kò dùn.
en400-yo400
Hallmarked by nonsense, 'The Culprit' is complete and utter rubbish!
òsì ni ènìyàn tó jẹ̀bi
en400-yo400
Had to watch it for academic purposes.
Mo nílò o láti wo fun ìwúlò ẹ̀ka ẹ̀kó
en400-yo400
Way too slow. What a waste of time.
Ó ti falè̩ jù. Ifàkókò ṣòfò lásán ni
en400-yo400
Booorrring.
Kò dùn.
en400-yo400
That movie is such a bad egg to Nollywood.
Eré oníṣe náà jẹ́ òbu ẹyin fún Nollywood
en400-yo400
I caught the Nollywood bug while watching Rattlesnake.
Nígbà tí mò ń wo sinimá Paramọ́lẹ̀, ohun tí Nọ́líwuùdù jẹ́ ṣẹ̀ṣẹ̀ yé mi ni.
en400-yo400
With all its ridiculous comical exaggerations and acting performances that fluctuate between over-acting and bad-acting.
Pẹ̀lú gbogbo kàrámọ̀ ìpani ni ẹ̀ẹ̀rín àti ìṣọwọ́ ṣeré tí ó ń fò sókè sódò láàrín ín pé wọ́n ti tẹșan mọ́ ọ jù àbí pé wọn kò tilẹ̀ ríi ṣe rárá.
en400-yo400
The production is all over the place, and most characters are not fully developed.
Ìsejáde ti wà ní gbogbo ibí, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun kíkọ́ kò ní ìdàgbàsókè ní kíkún.
en400-yo400
waste of time and resources
Ìfàkókò àti àwọn oun èlò ṣòfò ni sinimá yìí
en400-yo400
You will hate it
Wà á kórira rẹ̀
en400-yo400
Beautiful storyline BUT It was a waste of precious 2hrs
Eré naa dára ṣùgbọ́n ófi wákàtí méjì ṣ'òfò
en400-yo400
Try as hard as they may; 'Your Excellency' proved extensively impotent, failing to deliver on its campaign promises.
Sa gbogbo ipá tí o le sà; 'Ọlọlá jùlọ fi hàn pé òun ò k'ójú òṣùwọ̀n, nípa àìlè mú gbogbo ìlérí tó ṣe nigba tí ìbò m bọ̀ ṣẹ.
en400-yo400
Absolute Garbage. . Not even worth being filmed. Actors are weak, script was written by a 12 year old. Poor sound quality.
òṣì rándanràndan. . . . kò tó láti jẹ́ àwòrán . . Àwọn Òṣeré lẹ, Akọ ìwé náà láti ọwọ́ ẹni ọdún méjìlá. Ohùn wọn kò ká ojú òṣ̣ùwọ̀n
en400-yo400
Taking a scenic, soap-opera route through the Nigerian civil war of the 1960s turns out to be a navigational error from which this lavishly appointed production can never fully recover.
Gbígbé ojú ìwòye, ọ̀nà eré nípasẹ̀ ogun ábẹle Nàìjíríà tí àwọn ọdún 1960 yípadà láti jẹ́ àṣìṣe lílọ kiri nínú èyítí ìṣelọ́pọ̀ tí a yàn láwùjọ yíì kò le gbà padà pátápátá.
en400-yo400
However, this failed to be anything other than boring. It had no logical flow
Sibẹsibẹ, eyi kuna lati jẹ ohunkohun miiran ju alaidun. Kò mú ọgbọ́n wá rárá
en400-yo400
Very bad acting, but the movie is still entertaining.
Ìṣèṣe búburú púpọ̀, ṣùgbọ́n fíìmù náà tún j́ẹ ìdánilárayá.
en400-yo400
This was a No, No! Really bad performances from the main cast.
Èyí kò dáa rárá. Ìṣekúṣe gbá à ni àwọn òṣèré náà ṣe.
en400-yo400
Entertaining despite being flawed
O dun bí ó tilè jẹ́ pé àṣìṣe wà nínú rẹ.
en400-yo400
This movie feels like a mish mash of under-developed ideas with a half hearted romance thrown in.
fíìmù yí dàbí ǹkan lára asòpá pọ́ tì lábẹ́-ìdàgbàsókè ẹ̀rọ pẹ̀lú kan ìdàjì ọkàn láti fìfẹ́hàn sínú.
en400-yo400
The movie script cannot pass for a high school amateur production.
Ọmọ ilé ìwé ẹ̀kọ́ gíga gan-an ó ṣe àkóso fíìmù yìí.
en400-yo400
I dislike this movie so much
Mo kórira sinimá yìí gan-an ni ò
en400-yo400
The acting was SO bad and the writing was even worse.
Ìșọwọ́ ṣeré àwọn òșèré yẹn burú jáì, bí wón ṣe kọ eré náà tilè tún wáá burú bàjẹ́.
en400-yo400
The acting is at best wooden, the dialogue almost staccato, as if the actors are constantly being prompted with their lines.
Òṣèré náà wà ní igi tí ó dára jùlọ, ọ̀rọ̀ sísọ náà fẹ́rẹ̀ sí orin nínú , bí ẹnipé àwọn òṣèré nígbàgbogbo ní ìtara pẹ̀lú àwọn láìní wọ̀n.
en400-yo400
Everything about this movie speaks low budget
Gbogbo ohun tí ó wà nínú fíìmù yí ni ó sọ nípa isuna tí ó kéré
en400-yo400