sentence1
stringlengths 3
1.7k
| sentence2
stringlengths 3
1.73k
| lang
stringclasses 4
values |
---|---|---|
it is a great movie from someone whom we know to be a great storyteller. Gold Statue may not be one of Tade Ogidan’s best works, but it ranks high up there | Eré ńlá ni eré náà fún ẹni tí a mọ̀ sí olùsọ̀tàn àgbà. Gold Statue lè má jèé ọ̀kan lára àwọn eré Tádé Ògìdán tó dára jù o, ṣùgbọ́n iṣé ńlá ni iṣé náà. | en400-yo400 |
Nice movie. . . . Great story line. It was worth watching. I certainly would recommend watching it. | Ere gidi.. . . . Eré tí Ìtàn rẹ lágbára nìyí. Ó yẹ láti wò. Mo rọ yín láti wò ó. | en400-yo400 |
This was fun to watch. . . . The Delivery Boy is very refreshing, a beautiful story, told brilliantly. You should see it! | Èyí dùn ń wò. . Ọmọ a báni gbẹ́ ẹrú jíșẹ́ yẹn mú ìbàlẹ̀ bá ọkàn ẹni púpọ̀. Ìtàn gidi ti wọ́n sọ lọ́nà tó mú ọgbọ́n dání. Ó yẹ kí o wò ó. | en400-yo400 |
This show should have 5 seasons!!!!. . . . This show was so interesting and entertaining. If the real Caliphate has a problem with it. Change or abbreviate the name, abeg. Great cast!!! Great writing!!! Great visuals. :) | Ó ye kí eré yìí ni sísìn karùn-ún. . . . Eré yii dára yà àti pé ó dùn gan. Ti àwọn cálífátì kò bá ní ìfé si. Èyí orúkọ náà padà tàbí ke yọ kúrò lára rẹ̀. Òṣèré ńlá, eré kíko ńlá!! Àwòrán ńlá. | en400-yo400 |
Great movie. . . . I cannot for the life of me understand the low reviews for such a remarkable film. This series was so good that I binged the entire series as a Medical Student. Great work and thumbs up to the producer and casts. | Eré ńlá. . Mi ò ní òye ìdí tí eré ńla yìí fi ní àgbéyèwò tí ó kéré tó bayi.Eré náà dùn tí mo fi gbogbo ọkàn mi síi gẹ́gẹ́ bí ọmọ akẹ́kọ̀ ilé ìwòsàn.. . Ise takuntakun and òsùbà fún àwọn adarí àti olùgbéjáde Eré náà. | en400-yo400 |
The production was great a d light years ahead of most of the sub-par movies of African cinema. This movie is truly a great step in the right direction for Afican cinema. | Iṣẹ́ lọ́pọ̀ rẹ tí yọrí ju awọn akẹgbẹ rẹ̀ lọ ní orílẹ́-èdè Afirika. Fíìmù náà jẹ́ ìgbésẹ̀ àrà ní ọ̀nà tí o tọ fún ṣinimá Afirika. | en400-yo400 |
Entertaining live concert featuring lively arrangements of jazz and pop standards and an excellent orchestra | Orin atunilára tí ó sín pẹ́pẹ́ pẹ̀lẹ́ orin jáàsì àti pọ́ọ̀pù tí ó peregedé àti ẹgbẹ́ akọrin eléré ìtàgé tí ó kún ojú òṣùwọ̀n. | en400-yo400 |
This return of the king is glorious. | Ìpadàbọ̀ ọba náà dáa | en400-yo400 |
Great job!! | Iṣé ńlá. | en400-yo400 |
Well crafted, highly personal story told with superb acting | Àgbékalẹ̀ rẹ̀ gún régérégé, ìtàn tí ó kani lára gbọ̀ngbọ̀n tí a sọ pẹ̀lú ìṣèrè tí ọ dára gidigidi. | en400-yo400 |
Still one of the Best Nigerian films of 2017. . Isoken is a great film showcasing the culture of the area of the country. The layout, filming, colors and dressing tell much of the tradition quite well. The film has quite a good inject of laughter and great acting.. . | Ọ̀kan lára fíìmù tí a ṣe tó dára jù ni ọdún 2017 ni “Isoken”. Ere yìí sàfihàn àṣà tó wà ní agbègbè orílè-èdè tí a ti se é jáde. Àlàkalẹ̀ eré naa ati, ìgbàwòran jáde, àti àwọ̀ àti aṣọ ló se àfihàn àṣà ìbílẹ̀ ni. Ère yìí tún ní ọ̀kan ò jọ̀kan abala ti tó lè pa ènìyàn lẹrin ín. | en400-yo400 |
Great watch. . . . Great movie! I enjoyed the fact that they promoted the Igbo language! | Ó duǹ-ún wò.. . Eré gidi! Mo gbádùn pé wọ́n mú ìdàgbàsókè bá èdè igbo | en400-yo400 |
Hand-held camera chases, emotionally fraught close-ups, arresting compositions and a script that gives a familiar story a distinctly African flavor make "Òlòtūré" a thriller you not only endure but marvel over and embrace. | Àwọn àbí tí wọ́n fi kámẹ́rà àmúlọ́wọ́, àwọn abala tí ó tọ́ ni lọ́kàn, àpilẹ̀kọ tó gbọkàn kan àti ìkọ̀tàn tí ó fún ìtàn tí a ti mọ ní àwọn àmúyẹ ilẹ̀ Adúláwò ló jẹ́ kí ‘Oloture’ jẹ́ sinimá tó lágbára tí o ò kàn ní rọ́jú wò ṣùgbọ́n tí yóò yà ọ́ lẹ́nu tí o ó sì fẹ́ràn. | en400-yo400 |
You need to watch this!!!!!. . . . A must watch!!! I'm in love with the character The plot Literally everything | O nilo lati wo eyi!!!!!. . . . Agbọdọ wo !!! Mo feran ipa ti awon osere ko, itan naa, koda gbogbo re lapapo | en400-yo400 |
fantastic movie | Eré tí o dára . | en400-yo400 |
I love you - I have a baby… | Mo fẹ́ràn-an rẹ̀ - Mo ní ọmọ kan… | en400-yo400 |
A great piece of work by Kemi Adetiba, the story was well scripted, good cinematography, all actors gave a great performance. This is a world class movie... Kudos to the all the crews | Íṣe àrà làti ọwọ́ Kẹ́mi Adétiba, ìtàn náà ni akọsilẹ dáadáa, ìwà àkọọlẹ tí o yege. Gbogbo àwọn òṣeré ṣiṣe takuntakun. Fíìmù yìí jé ti àgbáyé,mo kàn sárá sí gbogbo ẹgbẹ awọn atuko | en400-yo400 |
Powerful film of a totally forgotten episode in history; not for the faint of heart. | Eré alágbára tí agbọn ìtàn tí a ti gbàgbé . Èyí kìí ṣe fún àwọn tí kò ní àyà. | en400-yo400 |
Great film - entertained and educated | Eré tó dára gan ni o sì kọ́ ní lọ́gbọ́n | en400-yo400 |
serious drama with subtle comedy, my type | Eré tí o lé ti ó sí ní àsìkò ẹ̀rín. Ìyẹn ní irú àwọn eré tí mo fẹ́ràn. | en400-yo400 |
Wow, this true story! Wow! Amazing. . . . Wow this story! The many many many stories of the Black experience throughout the African diaspora, and throughout generations. I am so glad our Brotha shared his story and got to write, direct, star in. And Damson wow, his acting is always amazing. | Itan tooto yii! O le kenka. . . . Ìtàn ńlá ni ìtàn yìí. Ìtan ìrírí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ adúláwò tí ó wá ní òkè òkun láti ìgbà ìwáṣẹ̀. Inú mi dùn pé arákùnrin wa sọ ìtan tirè, tí ó sì kọ ọ, darí, tí ò tún kópa nínú síṣe rẹ̀. Isé eré Damson dára púpọ̀. | en400-yo400 |
Impressive & funny how they portrayed both cultures. I was entertained all through! Clean cut production. | Ó mó rí wu , ósì pa ni lẹ̀rín bi wón ti ṣàpèjúwe àṣà méjèjì. Mo ni idálaráyá jálè ! Erè àgbéléwò to jágeree ní è yìí. | en400-yo400 |
Excellent delivery. . . . The movie is a wonderful delivery of the sexual assaults on university female student by some lecturer. It passes the message in a simple unsuspecting manner. Unpredictable end however, a few forgivable misses | Àgbéjáde tó tayọ.. . Fíìmù yí jẹ́ èyí tó sọ nípa ìkọlù ìbálòpọ̀ tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà lóri àwọn ọmọ obìnrin láti ọwọ́ àwọn olùkó. Ó ṣe ìfiránsé tó rọrùn ní ònà tí a kò lérò. Ònà tí a kò fọkàn sí, Ìpàdánù díẹ̀díẹ̀ wà níbẹ̀. | en400-yo400 |
Amazing. . . . Loved the display if pure culture even in the music. Great to see the people who made me watch nollywood movies again. All round thrilling and very funny.. | Iyanu!. . Mo fẹ́ràn ìfihàn àṣà àní ninu orin. Ó dára láti rí àwon ènìyàn tí ó mú mi wo eré Nollywood lẹ́ẹ̀kan si.. . Ósì mù ni rẹrin. | en400-yo400 |
Fantastic Series from Nigeria. . . . I love this series. Great scenery. Fantastic acting. Everybody was giving their A game. The jokes were natural and very relatable. It was educative as well. | Eré oní pele sí ipele tí Naijiria tó dára. . . . Mo féràn eré yìí. Ó dùn wò. Eré ṣíṣe tó dára. Gbogbo ènìyàn fakọ yoo. Àwàdà inú eré na jojú. Ó ṣì kó èèyàn lọ́gbón. | en400-yo400 |
Hits the right note. . The language is Street, the cast stellar, cinematography and editing is on point. It also has a great plot. Best of all it puts Ajegunle on the map. | Eré náà sọ ojú abẹ́ niko. . Èdè tí wọn ló jẹ èdè oríta, àwọn òṣèré náà ṣe bẹbẹ, ìgbé eré jáde àti ìsàtúntò naa dara lọ́pọ̀. Ó sì tún ní ìtàn tó dára. Pabambarì rẹ̀ ni wípé ó gbé Ajegunle sórí àwòrán ayé. | en400-yo400 |
New Pandemic that could happen again!. . . . It's a a brilliant movie and very realistic about what really happened. It's better than the movie Contagion in my book. It really hit close to home for me. It's one of the first serious pandemic in my lifetime. I would really like to purchase this movie on DVD and I've been look in the US but to no avail. Can someone tell me how? Thanks | Àjàkálè àrùn tó ṣì tún le ṣẹlẹ̀. . . . Ó jẹ́ eré tó tayọ, tó ṣì jẹ́ yọ pẹ̀lú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ni àyíká wa. Ó dára ju gbogbo àwọn eré tí mo ní lọ́kàn lọ. Eré na ṣàfihàn ohun tó pọ̀. Ó jẹ́ àjàkálè àrùn tó lágbára àkókó ni ìwàláàyè mi. Má nì fẹ́ láti ra kásẹ̀tì rẹ̀ ṣọ́wọ́, mo tí wá káàkiri US ṣùgbọ́n mí ó tí ríi. Ṣé amo bí tí mo tí lé e ri rà. | en400-yo400 |
How does a movie with this subject matter wind up being this slow and boring? Where is the urgency? Where is the suspense and tension? The editing and the pacing drove me nuts and there's just no way this thing needed to be nearly two and half hours long. And that's really a shame because it highlights a really big and important problem, I just wish it did so without putting the audience to sleep. | Bo ni o ṣe jẹ wípé eré tó ní irú akole yii se di wipe o lọrá ti o sí danilagara. Nibo ni ìkánjú wa? Nibi ni ifẹni sokunkun ati aibalẹ ọkan wa pẹlu? Isatunkọ ati iwọn rẹ bi mi nínú ti o sí ònà ti o fi je kí eré náà tó wakati meji at'abo. Nkan to dojutì ni ni wípé eré náà ṣàfihàn ìṣòro tó ṣe kókó, emi kan ro wipe won le eré náà lai mu kí àwọn oluworan ma sun. | en400-yo400 |
Lionheart is such a beautiful movie👏. . . . This movie is the best Nollywood movie I've seen so far. Every scene was precise, beautiful and with a touch of humour and a moral lesson. I like that Nigeria was well represented. | Lionheart jé eré tó lẹ́wà.. . Eré yìí jẹ́ eré ilé adúláwọ̀ tí ó dára jùlọ tí mo ti wò. Gbogbo abala eré náà dára, ó tún ní àwàdà díẹ̀ àti ọ̀rọ̀ akọ́nilọ́gbọ́n. Mo fẹ́ran wípé ó ṣojú Nàíjíríà dáadáa | en400-yo400 |
Season 2. . . . I loved Season 1 and I could hardly wait for Season 2. I like all the characters. So hopefully you'll keep bringing on the new Series. | Ìpín kejì. . Mo fẹ́ràn ìpín àkọ́kọ́ àti wípé mò ń fojú sọ́nà fún ìpín kejì. Mo fẹ́ràn gbogbo àwọn òṣèré náà. Mò ń sì ní ìrètí wípé àwon ìpín tuntun mìíràn yóò jáde. | en400-yo400 |
It was a 2hours movie that I rather shouldn't call entertainment but a moment of empowerment. If I was having doubts, my conviction got better... I was able to connect with the movie because obviously, I have experienced a touch of God before.. . . . I say "yes" again to God's call. | Eré náà jẹ́ eré oní wákàtí méjíì tí mi ò ní pè ní ìgbádùn ṣùgbọ́n ó jẹ́ àkókò ìrónilágbára. Tí mo bá ń ṣiyèméjì, ìgbàgbó mi tún ti lékan si… Eré náà yé mi dáadáa nítoripé ó dájú pé olórun ti fọwọ́ tó mi rí.. . . . Mo tún jẹ́ ìpè ọlọ́run léékàn si. | en400-yo400 |
It almost accurately portrayed the abuses a lot female students face in Nigerian universities and west Africa at large | Ó fẹ́ẹ̀ rí bí wọ́n ti ń ṣe àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin ni Nàìjíríà àti ìwọ oòrùn Áfíríkà báşubàşu. | en400-yo400 |
Colorful and detailing but thrilling isn't the word. . . . In general, Fifty is standard, beautiful and lively, it is expected to be thrilling at the end but the goose in my pimples didn't show off much but I was happy remembering few lines and scenes at the end. | Ó ní àwọ̀ àti àlàyé ṣùgbọ́n ìwúnilórí kìí ṣe ọ̀rọ̀ náà . . . . Ní gbogbogbò, Àádọ́ta jẹ́ bó ṣe wà , ó ní ẹwà àti iwunlere, ìrètí ni láti jẹ́ìwúnilórí ní ìparí ṣùgbọ́n kò wọ̀ mí ní akíyẹmí ara ṣùgbọ́n inú mi dùn tí mo bá ń rántí diẹ nínú àwọn ọ̀rọ̀ àti síìnì wọn ní òpin. | en400-yo400 |
Kunle Afo's most impactful movie so far... . . . The movie address a topic that is very fundamental in Nigeria Education system. Good story line, interesting plot, fantastic acting. This movie is one of the best you will ever watch on topics bothering on gender based violence in Africans higher institutions. Just enjoy it and firm your unbiased review! It's a cool one | Ise to lami laaka ti Kunle Afo se yi si eyin. . Eré yi mu enu ba oro to se koko si abala eko orile ede Naijiria. Itan to dara, ibEré to dun,sise Eré to mu ako yo. Fíìmù yi je Eré to dara ju lati wo lori koko oro lako labo ni ile eko agba ti ile adulawo. E gbadun re ki e si di atunyewo yin mu. Fíìmù to dara ni. | en400-yo400 |
A Brilliant Movie. . . . Just watched Lara and the Beat on Netflix. This film is wonderful. Beautiful cinematography, on point acting, a great story, nice music and wholesome entertainment that the whole family can enjoy. | Eré tó tayọ. . . . Mo ṣẹ̀ wo Lara ati Beat lóri Netflix .. . Eré yii ya ni lẹ́nu. Ìtanná eré tí ó rẹwà, eré síse tí ó wà n bẹ́, ìtàn tí ó lágbára, orin tí ó dára ati ìdárayá tí ó pé tí gbogbo ẹbí máa gbádùn. | en400-yo400 |
Refreshing. . Loved everything about it. The culture, language and music were beautiful. | Onítura. . . . Mo fẹ́ràn gbogbo nkan ní bẹ̀. Àsà, èdè àti orin naa rẹwà | en400-yo400 |
The movie authentically gives us the feel of the eighties, up to how parties were organized, the talk about bleaching, the clothes, and the generous use of damask and adire. | Eré náà láìsí àníàní fún wa níbí ǹkan ti rí ní ìgbà àwọn bàbáa wa, títí dé ibi ayẹyẹ ṣíṣẹ, ọ̀rọ̀lóríi bíbóra, àwọn aṣọ̀, àti bí wọ́n ti lo àwọn aṣọ àdìrẹ àti damask | en400-yo400 |
It's a well paced movie, filled with properly fleshed out characters operating in a plot structure that doesn't fall apart. The film. is brought o life with a stunning aesthetic and masterful cinematography. The story, although not phenomenal, is good enough to keep you glued to your seat while imparting a thing or two about the subject matter. | Eré tí ó ní ètò ní ó jẹ́, ó sì kún fún àwọn òṣeré tí wọ́n mọ iṣẹ wọn ṣe. Wọ́n gbé eré yí jáde pẹ̀lú ìmọ tó dánkiá nínú ètò ati ìdarí eré sinimá. Ìtàn inú eré, bó tí lẹ jẹ́ wípé kín ṣe pé ó dáa gán nà, sùgbón wọ́n gbìyànjú láti lè mú kí àwọn èèyàn jókòó tí eré náà. | en400-yo400 |
Season 2 Please!. . . . I watched "Fifty Series" and came upon Castle & Castle because of Tola face was familiar. I love this series and would love for a season 2 to come! I just hate that if left me hanging on the last episode, like a season 2 would be coming. So please give us a season 2!! | Sísìn ẹlẹ́kejì ejò ó!. . Mo wo “Fifty Series “ mo tún wo Castle & Castle torí ojú Tola faramí. Mo féràn eré oní pele sí ipele yìí, ma sí ní ìfé pé kí sísìn kejì jáde. Mí ò féràn pé ẹ́písòdù tó kù ló kù mí kù. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ fúnmi ni sísìn ẹlẹ́kejì oo!! | en400-yo400 |
Terrific film!. . . . This is an intense, heartbreaking family drama with an excellent script and stellar acting performances. | Sinimá yìí le o.. . Eré mọ̀lẹ́bí tó káni lára, pani lẹ́kún tí wọ́n rí ìtàn rẹ̀ kọ́ tí àwọn òșèré inú rẹ̀ sì rí ṣe. | en400-yo400 |
Light and funny!. . An absolute comedy gold with a great plot-line. From the sisters to the villains, this is a must watch! Not the mention the unexpected fantasy elements and great special effects! Highly recommended. | O fúyẹ́ o sí pa'ni l'ẹrin. . Ìdíyelé góòlù àwàdà pelu ìtàn tó dára. Lati ọ̀dọ̀ awọn arábìnrin dé orí awọn alátakò,o gbọdọ̀ wò. Ka na so ìdá pìlẹ̀ àlà aìròtẹ́lẹ̀ ati ipá pàtàkì! Mo gba yi. Níye kí ẹ wòó. | en400-yo400 |
They took a risk but the execution from production to acting was very well done. | Wọ́n farawọn wéwu ṣùgbọn ìgbéjáde eré náà dára. | en400-yo400 |
Farming may not be the best-executed story, but with a captivating performance by Damson Idris, nevertheless, it is still a story worth telling. | Àlàyé lè má jẹ́ ọ̀nà tó dára láti sàgbékalẹ̀ ìtàn, àmọ́ sá Desmond Idris sàgbékalẹ̀ ere yìí dáadáa bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ ìtàn àsọtúnsọ. | en400-yo400 |
SUPERBLY REFRESHING!!!. . . . Everything about this movie was just on POINT! The story line, characters and directing..down to costumes. I absolutely enjoyed this!! My popcorn was out in minutes! Love love love! Please make more movies!!! | Ó TU NI LÁRA!. . . . Gbogbo ǹkan tó wà nípa eré yìí ló dára! Ìtàn-àn eré náà, àwọn òṣèré, àti dídarí, títí dé àwọn ǹkan ìmúra. Mo gbádùn èyìí lọ́pọ̀! Gúgúrú mi tán-án ní ìséjú péréte! Mo fẹ́ràn rẹ̀ gaan! Ẹ jòwó, ẹ ṣe fíìmù síi. | en400-yo400 |
Nice cross-country movie. . . . The only thing that I don't like about this movie is the way there was little or no interaction with the Nigerian or Indian environment.. . . . Beautiful romantic movie. | Eré àgbéléwò dìdára lórí jákèjádò- orílè-èdè . . . . Oun kan pàtó tí mi ò féràn nípa fíìmù yìí ni pé ko si ibásepò pẹlu ágbègbè orílè-èdè Nàìjíríà ati india bó ti wu ó kéré mọ. . . . . Eré àgbéléwò ìfé tó lárindin lè yìí | en400-yo400 |
Amazing movie. . . . I loved loved watching this movie with its excellent plot, screenplay directing and Dakore and the cast delivered so well on the acting. Our culture and heritage was fully represented.Oscar worthy if it was in indigenous category. Definitely a 10/10 for me | Eré tó jọjú. . . . Mo fẹ́ràn láti máa wo ere yìí nítorí àkójọpọ̀ ìtàn rẹ̀, ìdárí àwòrán eré, dakore àti bí àwọn tó kó pa nínu eré náà se fakọyọ ninu ere síse. Wọ́n gbé àṣà ati ìṣẹ̀ṣe wa lárugẹ nínú eré náà. Ó yẹ́ kí ó gba àmì ẹ̀yẹ ọ́síkà tí ó bá jẹ́ pé ti wa n ti wa ni. Láì sí àní àní, eré náà gba ẹ́ẹ̀wá lori ẹ́ẹ̀wá láti ọ̀dọ̀ mi. | en400-yo400 |
A fantastic movie!!! Wow wow wow. Nollywood has ascended. | Eré orí ìtàgé dára jù. Nollywood tíì gòkè àgbà. | en400-yo400 |
Brilliant. . . . Good story line that requires so much attention. But overall, the movie is well done. | Fíìmù tó wuyì. . Ìtàn tó dára tó bẹ̀rẹ̀ fún àkíyèsí púpò.. . Ní gbogbo rẹ̀ jùlo, Fíìmù náà kú iṣé takuntakun. | en400-yo400 |
Great Movie from Nollywood.. . . . Lionheart wasn't just written for the sake of it. It portrayed so many things going on in Nigeria that it'll take one with in-depth and an open mind to see through the movie. | Eré nlá làti ọwọ́ọ Nollywood. . . . Wọn ò kọ̀ kọ erée Lion Heart lásán. ó fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun tí on ṣẹlẹ̀ ní Nàíjírìa hán ni gbàgede ti o ma gba eni tí ó bá farabalẹ́ tí ósì ní ojú inú láti rii ninu eré naa. | en400-yo400 |
This is by far the best production from nollywood! It looks more like an African American film. The acting is top notch and to find out it is the lead actresses first film, thumbs up. | Eré yii jẹ́ eré tí ètò rẹ̀ dára jù lọ lára eré Nollywood. Ṣe ló jọ eré Afíríkà àti Amẹ́ríkà. Eré ṣíṣe inu rẹ̀ nẹgba, ótún wá yani lẹ́ nu torí pé eré àkọ́kọ́ tí òsèré asíwájú kọ́kọ́ kó pa ninu rẹ̀ ni. Mo júbà. | en400-yo400 |
Something like a Shakespearean comedy, full of highly amusing, sharply drawn characters and offering wicked insight into how identity is shaped by city living and immigrant culture clash. | Ǹkan bí eré apanilérìn-ín ti Shakespeare, ó kún fún àwọn òṣèré adérìínpani tó o dámúsé, o sì fúnnú ní ìwòye tí ó dájú sí bi gbígbé nínú ìlú tó fi fúni nídánimò àti Ìja àda àwọn àrè. | en400-yo400 |
Nigerians in Brooklyn. . . . This is an amazing film, suspenseful, thoughtful, and colorful. | Àwọn ọmọ orílẹ́-èdè Nàìjíríà ní Brooklyn . . . . Èyí jẹ́ fíìmù ìyàlẹ́nu , ìfura, ìronú jinlẹ̀, àti àwọ̀. | en400-yo400 |
Temi Otedola did amazing job! | Ise takuntakun ni Temi Otedola se | en400-yo400 |
Thank you for a perfect example of how HE works in our lives: This movie is a gut-wrencher, reminding us how He works through imperfect, repentant people who are only called to obey Him. He does the rest. He is faithful to complete what He has started. What a GOD honoring movie, showing the Triune in goodness and glory and power. Thank you. | Ẹ ṣeun fún àpẹrẹ́ tí ẹ ṣe nípa bí Ó ti ṣe ń ṣiṣé nínú ayé e wa. Eré yìí ṣí ni lórí, ó rán wa létí bí ó ti máa ń ṣiṣé nípasè ẹ àwọn tí kò jẹ́ pípé tí wọ́n sì ní ìrònúpìwàdà tí wọ́n jẹ́ àwọn tí a pè láti gbọ́rọ̀ síi lẹ́nu. Òun ló ń ṣèyókù. Yóò parí iṣé tí ó ti bèrè. Eré tí ó bu ọlá fún ọlórun, tí ó sì ń fi oore, ògo, àti agbára métalọ́kan hàn. Ẹ ṣé púpọ̀. | en400-yo400 |
Stroyline was beautiful. . . . The plot twist was everything. Suspense filled. Gripping and interesting. Touched a lot on the importance of communication in relationships. I'll watch it over and over again. | Ìtàn náà rẹwà.. . Ìgbèrò eré náà dára púpọ̀. Ìrètí kíkún, àti ìfanimọ́ra. Ó fọwọ́ kan púpọ̀ lórí pàtàkì ìbánisọ̀rọ̀ nínú ìbásepọ̀. Màá tún Fíìmù náà wò ní orísirísi ìgbà. | en400-yo400 |
I love this film! I've watched it several times. I hope another one is in the works | Mo nífẹ̀ẹ́ eré yìí mo sì ti wòó fún àìmọ̣ye ìgbà. Mo sì retí òmíràn n bọ láìpẹ́. | en400-yo400 |
A Modern Nigerian Classic. . . . . . Nollywood truly has a political/religious/tribal gem here for those who seek to broaden their perceptions of the whys of the major ills of the world & in this case a small community in Nigeria - r so pervasive today.. . . . Soul comes to this physical reality for experiences & this film delivers a ton of them❤ | Ọmọ Nigeria ìgbàlódé aláìlẹ́gbẹ́. . . . Aájò oni sinima àgbéléwò ti Nollywood ni tòótọ́ ìwà òṣèlú, ẹṣin àti ẹ̀yà nigbonni yìí, fún àwọn tó bá fẹ́ fikún òye wọn nípa ìdí tí a fi ni àwọn òkè ńláńlá lagbaye. Nípa báyìí, àwọn ìletò kereje ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí farahàn lónìí.. . . . Ẹ̀mí ọkàn fara hàn nínú ojutaye nítorí orisirisi ìrírí, ìpín kan lára nǹkan wọ̀nyí ni sinima àgbéléwò yìí gbé síta. | en400-yo400 |
Fun to watch especially if u understand the Igbo language... But in general it's a good and interesting movie.. | Ó dun láti wò pàá pàá tí ó bá ní òye èdè Igbo ṣùgbọ́n ní gbogbogbò,o jẹ fíìmù tí o dára | en400-yo400 |
This movie feels like a mish mash of under-developed ideas with a half hearted romance thrown in. It is not sure if it wants to be a comedy or a satire. | Eré yìí dàbíi wípé ó jẹ àgbápọ̀ àwọn àbọ̀ odidi eré tí wọ́n tún fi eré ìfẹ́ sí. Kò jọ pé eré ẹ̀fẹ̀ lásán tàbí eré ẹ̀fẹ̀ àti sẹ ǹkan nínú ayé. | en400-yo400 |
Genevieve Nnaji proves yet again while she's still the best Nollywood actress of all time with her directing debut. we can only say more grease | Genevieve Nnaji tún fihàn lẹẹkan si wípé óun sì ni óṣèré Nollywood tí ó jáfáfá jùlọ pẹ̀lù ìtọ́sọ́nà eré alákọkọ. Ohun tí a ni la ti sọ nipé kí agbára naa kí ó ma pọ̀ si | en400-yo400 |
A film which captured a nation's hope for better cinema. . . . One can only wish that other Nigerian filmmakers will build on this same ground for a much brighter Nigerian film future. | Fiimu tó ṣàfihàn ìrètí orílè-èdè kan fun àyípadà sinemá tó dára. . . . Ìrètí ni pé àwọn alágbè jáde eré tí ń ṣe tii Naijiria náà le fọwọ́ ṣò wọ́pọ̀ torí ọjọ́ ọ̀la tó dára fún ilé-isé ìgbé fiimu jáde ti ìlú Nàìjíríà. | en400-yo400 |
Absolutely sensational. . . . This made me feel proud to be Nigerian. Storyline aside, the performances from each character wEré phenomenal and really captured my attention. | If̀ọ̀kànbalẹ̀!. . O fún mi ní igbéraga okan. Yàtọ̀ sí ìtàn, Isé òṣèré láti ọwọ́ àwọn òsèré jẹ́ ǹkan tó dára ó tún fa ọkàn mi mọ́ra. | en400-yo400 |
Searching for a soundtrack & review. . . . There'se a soundtrack at the end of the movie. On the background. It contains no words, it's more a melody. I'm trying to find the name of it.. . . . Beside that, great movie, really slow paced. Acting is realistic. No absurb emotions or anything like that. The conversations, the choosen words, the evens, the chemistry. It looks natural like you're watching a real situation. There's alot of silent moments and stuff like that. So you either like this type of movies, or you don't | Mo ń wá ohùn orin àti àgbéyẹ̀wò. . . . Ohùn orin kan wà ní ìparí Fíìmù náà. Ní abẹ́lẹ̀, kò ní ọ̀rọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohùn aládùn ni ó jẹ́. Mo ń gbìyànjú láti wá orúkọ rẹ̀.. . . . Lẹ́yìn ìyẹn, Fíìmù ńlá ni, ó fi àpẹ̀lẹ́ púpò tẹ̀síwájú. Ìṣọwọ́ṣeré rẹ̀ bòjúmu. Kò sí ìmọ̀sílára tàbí ohunkóhun bíirẹ̀ tí kò bòjúmu. Àwọn ìbánisọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ tí wọ́n yàn láti sọ, àwọn ìbádọ́gba, ìfanimọ́ra ní ọ̀tún àti òsì. Gbogbo wọn ló bá ìwà ẹ̀dá mu bí ẹni ń wo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ lójú ayé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àsìkò ìdákẹ́rọ́rọ́ àti ohun bíirẹ̀ wà. Nítorínâ, o ní láti fẹ́ràn irú Fíìmù yìí àbí kí o mâ fẹràn rẹ̀; kò sí wíwà ní àárín méjì. | en400-yo400 |
my number one nigeria sci fi best movie. . I love the movie, it falls into my favorite type which i am satisfy off, looking forward for nigeria to bring more to screen.. . . . And my advice for us Nigerian is to support this movie to encourage them to bring and produce more better movies of our choice for us to watch. | Àkókó nípò àwọn eré Nàìjíríà ti mo féràn jù.. . Mo ni ìfé eré náà, ó bọ́ si ọ́kan lára eré tó má ń tèmi lọ́rùn.. . . . Igbiyanju mi ni pé kí àwọn ará ìlú Nàìjíríà gbárúkùtì eré náà láti ri pé gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ re jáde láti wòó. | en400-yo400 |
Kemi Adetiba's King of Boys is exceptional. From the selection of cast to the well executed story line, this movie is nothing short of excellent. The thrill, plot twists, humor, unpredictability are unmatched. | Kémi àdetibà King Of Boys kọjá àdému ròyìn. Lat'ori yíyan àwọn òṣeré títí tó fí dé ṣíṣe ìtàn inú eré orí ìtàgé yìí. Eré orí ìtàgé yìí dára gan ní gbogbo ètò bí wọn ṣe ṣẹ o múná dóko. | en400-yo400 |
Perfection. . . . Someone should please help me find a mistake in this movie because I have watched it four times and still I can't find one. Everything about the movie was perfect. The movie is an original. | Pípé. . Kí enìkan jọ̀wọ́ bámi wá àbàwọ́n nínú ré yí nítorípé mo ti wò ó nígbà mérìn-in. . ati wipe emi ko ri abawon kankan ninu re. Gbogbo nkan nipa Eré na ni o pe. Ojulowo ni Eré na | en400-yo400 |
This film is is a true story and is absolutely brilliant and moving. | Ere yìí jé ìtàn tòótọ́ tí ó sì jẹ ìṣe ọpọlọ | en400-yo400 |
A Refreshing Nigerian Series. . . . Such a refreshing Nigerian series to watch without the awful music playing throughout the movie. However. I don't like that Netflix just carried Season 1, got me piqued and their is no season 2 to be found. | Eré Naijiria oní pele sí ipele to ní ìtura. . . . Eré ti Nàìjíríà tó fún ni itura tó ṣì dùn wò, tí kò sì sí àwọn orin buburu tí a kọ níbè. Mí ò féràn pé sísìn kan péré ní netiflesi gbé níbè. Kò dùn mo mi pé mí ò lè rí sísìn kejì. | en400-yo400 |
If it were food I would say mouth watering. . . . The film citation is a necessity, I do not see where it would ever run out of relevance. The actors were carefully picked and displayed such professionalism, the location were amazing never new had such good universities in Senegal , the arts and craft of our African leaders carved out the African identity.. . . . The message this movie carries, how it was told is so special, insightful and artistic. The suspense is on another level, the melange of feelings it creates to us the viewers is something else.. . . . Citation is a must watch go watch it on NETFLIX | Tí ó bá jẹ́ oúnjẹ ni máa ní ó bu omi rẹ ẹnu . . . . Àgbọdọ̀ wò ni fíìmù 'citation' jẹ́, mi ò ri bí ohun tó le kù tà. Wọ́n fi ara balẹ̀ yan àwọn Òṣèré náà wón sì fi àmì ògbóǹtagì hàn, àwọn ibi tí wón lò dára lọ́pọ̀lọpọ̀ mi ò sì mọ̀ pé àwọn ilé ìwé gíga tí ó dára wà ní Senegal, àwọn ọnà àwọn adarí wa ní Áfríkà gbé àmì ìdáni mọ̀ Áfríkà yọ. . . . . Ẹ̀kọ́ tí ó wà nínú eré yìí, bí wón ṣe sọ ìtàn naa jẹ́ ọ̀nà tí ó ṣe pàtàkì, tí ó ní òye àti iṣẹ́ ọnà tí ó peléke. Ìdádúró náà wà ní ìpele mìíràn, ìdàpọ̀ ti àwọn ìkùnsínú tí ó dá sí àwa oluùwò jẹ́ ǹkan mìíràn. . . . . Citation jẹ́ ohun tí o gbọ̀dọ̀ wò lọ wòó lórí NETFLIX | en400-yo400 |
Excellent Film. . . . This was a great film. A very simple storyline that provides a glimpse into the past to two boys (with many unknowns).. then the twists and turns that surround their reunion as grown men.. . . . Well done! So different from anything I've ever scene. | Fíìmù tó peregedé. . Fíìmù dára púpọ̀. Ìtàn tí kò rújú rárá tó sọ nípa àwọn ọmọ ọkùnrin méjì pẹ̀lú ìgbésí ayé tí wọ́n ti gbé sẹ́yìn tí àwọn ènìyàn kò mọ̀. Lẹ́yìn èyí ni àwọn kòtò àti gegele tó yí bí wọ́n ṣe padà ríra wọn nígbà tí wọ́n ti dàgbà.. . Ẹ kú ișẹ́. Èyí yàtọ̀ sí àwọn èyí tí mo ti ń wò tẹ́lẹ̀. | en400-yo400 |
Loved it. . . . ... beautiful movie ... i love my Nigerians. Beautiful storyline too . Well done | Mó fẹ́ràn rẹ̀. . . . erè ti o rẹwà... Mo fẹ́ràn àwọn ọmọ Naijiria mi. ìtàn erè naa dara. Ekú iṣẹ́. | en400-yo400 |
Beautiful, beautiful, sad and necessary. | Ó lẹ́wa, ó lẹ́wa, ìbànújẹ́ àti ìṣe kókó. | en400-yo400 |
My Village People delivered fantastic special effects, and they are not over the top. One of my favourite special effects is the rain. The technical crew deserves special recognition for their skills in this movie | My Village People ni àwọn isé sinimá tó dára kan tí wọn kò sì ní àṣejù. Ara àwọn isé yìí ni òjò náà. Àwọn onímọ̀ ẹ̀rọ náà yẹ fún ìgbóríyìn fún iṣé takuntakun tí wọ́n ṣe. | en400-yo400 |
Historic, Thrilling, Educative and Awesome | Ó dá lórí ìtàn, ó ń wúnilórí, ó ń kọ́ni lógbón, ó sì dára jọjọ. | en400-yo400 |
This is my favourite Nigerian film. Really enthralling debut feature. | Eré Naijiria ti mo yàn fẹ́ niyi. Ó dára nípasẹ̀ àwọn ẹ̀yà tí ó ní. | en400-yo400 |
I deeply appreciated seeing a movie with an emotional bond between two sisters who were connected in so many ways, but disconnected by romance and political views. The movie actors were superb and each character was perfectly cast for their roles. | Mo máa ń gbóríyìn fún fíìmù tó fi okùn ìfẹ́ tó gbópọn sáàárín àwọn ọmọbìnrin méjì tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan so papọ̀ ṣùgbọ́n tó jẹ́ pé ọ̀rọ̀ ìfẹ́ àti òṣèlú ló yà wọ́n sọ́tọ̀. Àwọn òṣèré tó kópa nínú eré yìí fakọyọ. Oníkálukú wọn ló kó ipa tirẹ̀ dáadáa. | en400-yo400 |
An Educational But Visceral & harrowing Film Expertly Crafted. . It's A great movie well acted and Directed Expertly Crafted while Being educational to a degree but it's a fully immersive visceral experience .. . . . Exploring Race ,and Gang Culture ,in England it's hard to believe some of these things Knowing that it was based on true story makes it and even tougher pill to swallow .Maybe a few scenes are for theatrical licence but still it comes from some where real .. . . . There's so many point in the film where i'd just ask why ? why would you do that ! Nooo !. . . . it's not for the faint hearted and it kind of messes with your mind it's the kind of movie that will leave you with many questions. . . . entertaining but thought provoking and intriguing A work of art One of the Most Original Movies I've seen in ages a refreshing perspective Definitely worth a watch | Ere akọ́nilọ́gbọ́n, ṣùgbọ́n tí ó ń wọ inú akínyemí ara ènìyàn pẹlú ìrora. Àgbékalẹ̀ pẹlú ìmòye tí ó lágbára. . . Fíìmù ńlá tí wọ́n ṣe tí wọ́n sì darí pẹ̀lú ìmòye. Àgbékalẹ̀ rẹ̀ ń kọ́nilọ́gbọ́n sí ipele kan, ṣùgbọ́n ó kún fún ìrírí tí ó ń ki ni sínú ìrora... . Ó ń ṣàwarí ẹ̀yà àti ìṣesí àwọn ọmọ jàgídíjàgan, ní orílẹ-èdè England, ó ṣòro láti gba àwọn oun tí ó ṣẹlẹ̀ nínú rẹ̀ gbọ́, ìmọ̀ wí pé Fíìmù náà dálórí oun tí ó ṣẹlẹ̀ lójú ayé tún bọ̀ sọ́ di òtítọ kíkorò. Bóyá awọn abala kan wà níbẹ̀ tí wọ́n jẹ́ fún ìṣèré lásán, ṣùgbọ́n ó sì wà láti ohun tí ó dìídì ṣẹlẹ̀.. . . . Àwọn ibi kan wà nínú sinemá àgbéléwò tí màá kàn bèèrè pé: “Kílódé"? Báwo ló ṣe máa ṣe bẹ́yen? Rárááá!.. . . . Kò wà fún àwọn ọlọ́kàn yẹpẹrẹ, ó sì ń sẹni lọ́kàn básubàsu. Ó jẹ́ eré Fíìmù tí yóò fi ọ́ sílẹ̀ pẹ̀lú òpòlopò ìbéèrè. Ó ń dánilárayá ṣùgbọ́n áá fa àròjinlè àti ìdáhùn sí yọ. Iṣẹ́ ọnà. Ọkàn nínú àwọn ògidì ere tí mo ti wò ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn. Àfojúsùn tuntun tí ó tọ́nà láti wò. | en400-yo400 |
It was a nice, wholesome movie about Love, Faith, Family and temptations of the world.......was a bit cheesy, but I enjoyed it. Fell in love with Mawuli Gavor and would watch it again just to see him.. | O jẹ fíìmù tí ì dára tí o sí ní anfààní nípa òrò ìfẹ, ìgbàgbọ, mọlẹbi ati ìdánwò ayé,ko pẹ ojú òṣùwọ̀n ṣugbọn mo gbádùn rẹ, mo nifẹ Mawuli Gavor má tún wo lati rí ní ẹ̀kàn si. | en400-yo400 |
Beautiful movie depicting historic events in Benin kingdom. . . . This movie was very educational and interésting to watch. I am still in shock it was done in 2014. The acting and directing was superb. . Kudos to the cast and crew. | Eré aladidun ti o ni awon isele itan Benin Kingdom ninu.. . Ére yìí kọ́nilékọ̀ọ́ púpọ̀, ó sì dùn-ùn ní wíwò. Ó sì yàmílẹ́nu wípé ọdún 2014 ni wọ́n ṣe é. Ìṣe eré náà àti dídarí rẹ̀ dára gaan gidi.. . . . Ìgbóríyìn fún àwọn tó kópa nínú síse eré náà. | en400-yo400 |
Great concept. . . . Creative storyline with talented actors. A bit excessive with some of the flashbacks but still very interesting throughout. | Àgbékalẹ̀ ńlá.. . . . Ìtàn tó mọ́pọlọ wá lárà ọ̀tọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣèré tí wọ́n mọ iṣẹ́ wọn níṣẹ́. Ìmọ́lẹ̀ títán sí àtẹ̀yìnwá ọ̀rọ̀ pọ̀ lápọ̀jù dìẹ̀ ṣùgbọ́n ó wuni láti ìbẹ̀rẹ̀ dópin. | en400-yo400 |
so cool. . . . This was so chilled. this movie was fun and enjoyable from the start. I've found no flaws to it, maybe the introduction is a little corny, but thats just taste. this movie was light but meaningful. highly recommended! | Ó mà dára o.. . Láti ìbẹ̀rẹ̀ ni sinimá yìí tí dùn. N kò tíì rí àṣìṣe kankan. Lóòótọ́, ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ rí bákan àmọ́ bí wón ṣe fẹ́ kó rí nìyẹn. Ata kéré iyọ̀ dùn ún ni fíìmù yí.. . Mo gbà yín níyànjú kí ẹ lọ wò o. | en400-yo400 |
KOB is Number 1 Nollywood movie to me right now. The story is way different and genuine. Unveils what goes on in politics for real. | KOB ni ó gbégbá orókè jù fún èmí laarin àwọn eré orí ìtàgé tó kù lọ́wọ́lọ́wọ́ yìí. Eré náà fí bí òṣèlú ṣe rí lójú ayé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. | en400-yo400 |
This was an excellent movie. I would recommend it to anyone! | Sinimá to lè kenkà lèyí. Mà á fi ọwọ́ rẹ̀ sọ àyà fún ẹnikẹ́ni láti wò ó. | en400-yo400 |
Love this Film. . I will enjoy watching it for many years to come and the conversations that it will spark. . . The acting is very natural without melodrama and it feels very believable. Overall, the film was riveting and kept me really engaged. | moféràn eré yí . . mà á gbádùn kin ma wó fún ọ̀pọ̀lopọ̀ odún tí ó nbò àti òrò àbásọ tí ó ma ń múwá. . Eré ṣíṣe lo létò láìsí orin aládùn, ó ṣe gbàgbó. Ju gbogbo ẹ lo, eré na dára, ó gba àsìkò mi. | en400-yo400 |
Love this Film | Mo féràn eré yìí | en400-yo400 |
A BRILLIANT MOVIE WITH A FEW PECKS | FÍÌMÙ TO GBÁMÚSÉ PẸ̀LÚ ORÍYÍN DIẸ́ | en400-yo400 |
Beautiful story that portrays Nigerian culture. The story is so unique and unpredictable unlike an average Nigerian movie. A must watch | Ìtàn to lewa ti o ṣàfihàn àṣà ilẹ Nàìjíríà. Ìtàn náà yàtọ ti o sí nira lati lè mọ ìparí rẹ gẹgẹ bi awọn eré Naijiria miiran. Agbọdọ wo ni eré náà | en400-yo400 |
A must see, very interesting story and well acted, great collaboration with Hollywood and Nollywood actors. I thoroughly enjoyed it. | Eré tí èèyàn gbọdọ̀ wò ni, ìtàn tí ó dára tí wọ́n sì ṣe dáradára pẹ̀lú àkójọpọ̀ àwọn òṣèré Hollywood àti Nollywood. Mo gbádùn-un rẹ̀. | en400-yo400 |
Fresh POV. . It is not the kind of cinema we are used to in the western hemisphere, but the production highlights not only a story to develop, but also the colors and culture of the region in which it takes place. | POV tuntun . . Kì í ṣe irú sinima ilẹ̀ òkèèrè tí a mọ̀. Kì í ṣe pé ìgbéjáde rẹ̀ sọ̀rọ̀ nípa ìtàn tí a fẹ́ gbésókè nìkan, ó tún sàfihàn àṣà agbègbè tí a ti ṣe eré náà | en400-yo400 |
"Citation" works best when it hovers in the infuriating skepticism hurled at its young protagonist as she makes her case, and it's unclear whether the system will work in her favor until the final, unnerving act. | Eré Citation ṣe iṣẹ gidi nígbàtí o ṣàfihàn ìgbàgbọ òṣèré pàtàkì àti bí wón se gbógun tó nígbà tí ó sàlàyé oun tí ó ṣẹlẹ̀ sí, bésìnì lákọ̀kọ́ó kò ye ni bóyá ìdájọ́ náà yóò ṣàfàní fún òṣèré náà Àbí yóò ṣe àkóbá fún. | en400-yo400 |
In a movie which seems like it should have been a mini-series, we follow a relationship, which grows into a family, over the course of 20 years in Nigeria. | Nínú eré tó dàbí eni ti o tó yẹ kó jẹ́ ere tí à ń sáfihàn rẹ̀ díẹ̀díẹ̀, a rí ìbáṣepọ̀ lásán to sì tẹ̀síwájú di ẹbí láàrin ọkùnrin àti obìnrin. | en400-yo400 |
Finally, a good one. . . . A solid entry from the stables of Ayo Makun that combines genuine comedy with love at heart. A must watch for all Nigerians. | Nígbẹ̀yìngbẹ́yín, a padà rí èyí tí ó dára.. . Láti ọwọ́ AYỌ̀ MÁKUN, eléyìí múná d’óko. Ó pá ẹ̀fẹ̀ gidi àti ìfẹ́ ọkàn papọ̀. Àgbọdọ̀wọ̀ ni fún gbogbo ọmọ Nàìjíríà. | en400-yo400 |
The best Nigerian movie I've ever seen. . This movie is amazing! Very creative and not predictable. I love how the story line is current and relates to what is going on in Nigeria at the moment. The acting was great - Sola Sobowale is a legend! | Fíìmù orílè-èdè Nàìjíríà tó dára jùlọ tí mo yí rí, fíìmù yìí yá ní lẹ́nu, alátiúdá púpọ àti alailọwaya. Mo fẹràn ni ìtàn náà se jẹ́ ti òde òní,tí o sí tún n'isẹ pelu òun tí o nlọ ni orílè-èdè Nàìjíríà lọwọ yìí, iṣẹ́ àrà ní . Alayé ní Ṣọlá Sobowale jẹ́ | en400-yo400 |
It's a superb piece of work: fresh, harrowing and very humane | Iṣẹ́ ọwọ́ tí ó fákọyọ: o jẹ́ tuntun, ó wà pẹ̀lú ìrora àti ìfọmọènìyànṣe | en400-yo400 |
Good series. . I'm really impressed with this series. Its captivating and entertaining. | Ipele eré tó dára. . Orí mi wú si ipele eré yìí. Eré aládùn tó tún mo ní mólè. | en400-yo400 |
I love this movie. . . . This movies is a very good movies and I wish it will still continue and please when is the season three and four going to be released . | Mo fẹ́ràn fíìmù yìí. . . . eré yìi ́jé eré tó dára púpọ̀ ó sì wù mí tí ó bá tẹ̀síwájú. Ẹ jọ̀wọ́, ìgbà wo ni ìpín kẹẹ̀ta àti ẹ̀kẹẹ̀rin yóò jáde? | en400-yo400 |
This is the reality of being a fault first child in affluent African homes.. . This movie is the reality of the struggle of being female in a male dominated and controlled African environment. | Eleyii fi òtítọ́ múlẹ̀ bii àkọ́bí nínú ilé olówó áfíríkà. Eré tó fi wàhálà ti àwọn obìrin máá n kojú ní àwùjọ tí ọkùnrin jẹ́ ojúlówó ọmọ nì ìlu Afirika. | en400-yo400 |
Wonderful story. . . . The movie has a lot of moral lessons. Great role interpretation by Zainab Balogun. If you have lost your way, this movie all you need to re-direct your path to God. | Ìtàn tó lágbára . . . . Eré yìí ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ nínú. Zainab Balogun túmò ipa náà dáadáa. Tí o bá ti sọnù, ǹkan tí o nílò ni eré yìí, yóò sì tọ́ ẹ sónà padà sí ìlànà ọlọ́run. | en400-yo400 |
A provocative if slightly plodding movie… | Ere to ń ru ènìyàn nínú tó sì fà nílẹ̀ | en400-yo400 |
Technically, the sound is very good, and camera angles and techniques are unusual and interesting. The fight scenes are well choreographed. | Nípa ti ìmọ̀ ẹ̀ro, ohùn náà dára púpò, béè sì ni àwòrán yíyà yáàtọ̀ sí ti àtẹ̀yìnwá tí ó sì dára. Wọ́n ṣe àwọn ìran ìjà náà dáradára. | en400-yo400 |