diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ìgbésí ayé Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì náà jẹ́ àpẹẹrẹ bí ìgbésí ayé Jésù ṣe máa rí .
Igbesi aye Solomoni omo Dafidi naa je apeere bi igbesi aye Jesu se maa ri .
Tom jẹ́wọ́ pé : “ Ńṣe ni oorun gbé mi lọ . ”
Tom jewo pe : “ Nse ni oorun gbe mi lo . ”
Ṣé wàá lè gba àwọn nǹkan míì tẹ́ni náà bá sọ fún ẹ gbọ́ nípa àwọn ohun tó túbọ̀ ṣe pàtàkì bí ohun tó o fẹ́ fi ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe ?
Se waa le gba awon nnkan mii teni naa ba so fun e gbo nipa awon ohun to tubo se pataki bi ohun to o fe fi igbesi aye re se ?
Ayọ̀ àti inúdídùn ni a ó rí nínú rẹ̀, ọpẹ́ àti ariwo orín kíkọ
Ayo ati inudidun ni a o ri ninu re, ope ati ariwo orin kiko
Síbẹ̀ , ṣó burú tí ẹni náà bá sọ pé láti ìbẹ̀rẹ̀ lóun tí máa wo eré náà ?
Sibe , so buru ti eni naa ba so pe lati ibere loun ti maa wo ere naa ?
Lẹ́yìn ìrìn àjò míṣọ́nnárì ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Pọ́ọ̀lù rìn , ó jábọ̀ fún ẹgbẹ́ olùṣàkóso nípa bí àwọn èèyàn ṣe yí padà .
Leyin irin ajo misonnari eleeketa ti Poolu rin , o jabo fun egbe olusakoso nipa bi awon eeyan se yi pada .
Mèsáyà máa wọ Jerúsálẹ́mù tiyì - tẹ̀yẹ .
Mesaya maa wo Jerusalemu tiyi - teye .
Ọ̀pọ̀ yóò wẹ ara wọn mọ́ , wọn yóò sì sọ ara wọn di funfun , a ó sì yọ́ wọn mọ́ .
Opo yoo we ara won mo , won yoo si so ara won di funfun , a o si yo won mo .
“ Àṣàrò inú ọkàn - àyà mi yóò sì jẹ́ ti àwọn ohun òye . ” — Sáàmù 49 : 3 .
“ Asaro inu okan - aya mi yoo si je ti awon ohun oye . ” — Saamu 49 : 3 .
Láti ọdún 2001 ni orílẹ̀ - èdè Àméníà ti di ara Ìgbìmọ̀ Ilẹ̀ Yúróòpù .
Lati odun 2001 ni orile - ede Amenia ti di ara Igbimo Ile Yuroopu .
Kí la lè sọ nípa òfin irú Ẹlẹ́dàá bẹ́ẹ̀ tàbí nípa Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tó wà lákọsílẹ̀ ?
Ki la le so nipa ofin iru Eledaa bee tabi nipa Oro re to wa lakosile ?
Ìgbéraga wọ̀ mí lẹ́wù débi pé mo kọ ìmọ̀ràn táwọn alàgbà fún mi , mo sì fi ìjọ Ọlọ́run sílẹ̀ . ”
Igberaga wo mi lewu debi pe mo ko imoran tawon alagba fun mi , mo si fi ijo Olorun sile . "
Nígbà tí Jésù kú tó sì gbé ìtóye ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ fún Bàbá rẹ̀ lọ́dún 33 Sànmánì Kristẹni la fi ìpìlẹ̀ májẹ̀mú tuntun yìí lélẹ̀ .
Nigba ti Jesu ku to si gbe itoye eje re lo fun Baba re lodun 33 Sanmani Kristeni la fi ipile majemu tuntun yii lele .
Ìyá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí bàbá rẹ jẹ́ ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì.
Iya re je omo ile Naijiria nigba ti baba re je omo ile geesi.
Nígbà tí Jésù wà lórí ilẹ̀ ayé , báwo ló ṣe tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Baba rẹ̀ ?
Nigba ti Jesu wa lori ile aye , bawo lo se te le apeere Baba re ?
Ọmọbìnrin rẹ ni ìwọ kò gbọ́dọ̀ fi fún ọmọkùnrin rẹ̀ , ọmọbìnrin rẹ̀ sì ni ìwọ kò gbọ́dọ̀ mú fún ọmọkùnrin rẹ . ”
Omobinrin re ni iwo ko gbodo fi fun omokunrin re , omobinrin re si ni iwo ko gbodo mu fun omokunrin re . "
gbọn-ọ́n
gbon-on
Jèhófà fẹ́ kó o di ọ̀rẹ́ òun .
Jehofa fe ko o di ore oun .
Àwòrán oníhòòhò máa ń ba gbogbo àwọn tó bá kó sínú páńpẹ́ ẹ̀ láyé jẹ́ ni .
Aworan onihooho maa n ba gbogbo awon to ba ko sinu panpe e laye je ni .
A lọ síbẹ̀ , wọ́n sì pín fọ́ọ̀mù Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì lé wa lọ́wọ́ lẹ́yìn ìpàdé náà .
A lo sibe , won si pin foomu Ile Eko Giliadi le wa lowo leyin ipade naa .
Ní October 1949 — ọdún mẹ́ta lẹ́yìn tí Bill gbé Rose níyàwó àti oṣù mẹ́ta lẹ́yìn tí wọ́n bí Vicki , ọmọbìnrin wọn — wọ́n sọ fún Bill pé kókó ọlọ́yún kan ń dàgbà nínú ọ̀kan lára àwọn tán - án - ná rẹ̀ , wọ́n sì mú kókó náà kúrò .
Ni October 1949 — odun meta leyin ti Bill gbe Rose niyawo ati osu meta leyin ti won bi Vicki , omobinrin won — won so fun Bill pe koko oloyun kan n dagba ninu okan lara awon tan - an - na re , won si mu koko naa kuro .
Báwo la ṣe lè dáàbò bo ara wa tá ò fi ní ní ẹ̀mí tí kò dára táwọn tí kì í jọ́sìn Jèhófà ní ?
Bawo la se le daabo bo ara wa ta o fi ni ni emi ti ko dara tawon ti ki i josin Jehofa ni ?
A sáà mọ̀ pé “ ayé ń kọjá lọ , bẹ́ẹ̀ sì ni ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ rẹ̀ , ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ni yóò dúró títí láé . ”
A saa mo pe “ aye n koja lo , bee si ni ifekufee re , sugbon eni ti o ba n se ife Olorun ni yoo duro titi lae . ”
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Awon Ohun To Wa Ninu Iwe Yii
Àwọn tó ń gbé orí àwọn òkè wọ̀nyẹn ní ẹ̀mí aájò àlejò gan - an ni .
Awon to n gbe ori awon oke wonyen ni emi aajo alejo gan - an ni .
yòò sì wí pé, 'Kì í ṣe àwa ni ẹ̀yin n
yoo si wi pe, 'Ki i se awa ni eyin n
Nínú ìwádìí kan tí Claude Steiner tó jẹ́ afìṣemọ̀rònú ṣe , ó parí èrò sí pé fífún ẹnì kan ní ìṣírí lọ́rọ̀ àti níṣe ṣe pàtàkì fún un láti ní ìbàlẹ̀ ọkàn láìka ọjọ́ orí rẹ̀ sí .
Ninu iwadii kan ti Claude Steiner to je afisemoronu se , o pari ero si pe fifun eni kan ni isiri loro ati nise se pataki fun un lati ni ibale okan laika ojo ori re si .
Àwa ńkọ́ ?
Awa nko ?
Láàárín ọjọ́ díẹ̀ péré , ó lé ní ọ̀kẹ́ mẹ́rin ààbọ̀ [ 90,000 ] èèyàn , ìyẹn ìpín méjì nínú ìpín ọgọ́rùn - ún àwọn àgbàlagbà tí wọ́n kó lọ sáwọn ẹ̀wọ̀n àtàwọn àgọ́ ìṣẹ́níṣẹ̀ẹ́ tí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn wọ́n pé wọ́n ń ta ko ìjọba Násì .
Laaarin ojo die pere , o le ni oke merin aabo [ 90,000 ] eeyan , iyen ipin meji ninu ipin ogorun - un awon agbalagba ti won ko lo sawon ewon atawon ago isenisee ti won si fesun kan won pe won n ta ko ijoba Nasi .
Tó o bá fẹ́ fi ọrẹ ṣètìlẹyìn , jọ̀wọ́ lọ sórí www.jw.org /⁠ yo .
To o ba fe fi ore setileyin , jowo lo sori www.jw.org /⁠ yo .
Bákan náà, Bísí Ògúnṣínà (1981:4) ki defined sociology Soṣíọ́lọ́jì báyìí pé:
Bakan naa, Bisi Ogunsina (1981:4) ki defined sociology Sosioloji bayii pe:
Jèhófà máa ń fi inú rere onífẹ̀ẹ́ tó ní , tàbí ìfẹ́ dídúróṣinṣin rẹ̀ hàn ní onírúurú ọ̀nà .
Jehofa maa n fi inu rere onifee to ni , tabi ife didurosinsin re han ni oniruuru ona .
dàmáskù
damasku
Nígbà tí Juan Arias ń sọ̀rọ̀ nípa ipa tí wọ́n ní Màríà Magidalénì kó , ó sọ nínú ìwé ìròyìn Brazil náà , O Estado de S .
Nigba ti Juan Arias n soro nipa ipa ti won ni Maria Magidaleni ko , o so ninu iwe iroyin Brazil naa , O Estado de S .
Ìwé Sekaráyà 13 : ​ 4 - 6 sọ pé kódà àwọn kan lára àwọn àlùfáà á jáwọ́ nínú ìsìn èké tí wọ́n ń ṣe , wọ́n á sì sẹ́ pé àwọn ò ṣe ìsìn èké rí . ​ — 7 / 15 , ojú ìwé 15 sí 16 .
Iwe Sekaraya 13 : 4 - 6 so pe koda awon kan lara awon alufaa a jawo ninu isin eke ti won n se , won a si se pe awon o se isin eke ri . -- 7 / 15 , oju iwe 15 si 16 .
( Wo Sáàmù 32 , 23 , 145 , 8 , 30 , 38 , 72 , 51 , 86 àtàwọn àkọlé wọn . )
( Wo Saamu 32 , 23 , 145 , 8 , 30 , 38 , 72 , 51 , 86 atawon akole won . )
Èyí jẹ́ ká rí i pé Awímáyẹhùn ni Jèhófà .
Eyi je ka ri i pe Awimayehun ni Jehofa .
Ọlọ́run sọ ọ́ nínú Òfin tí ó fún orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì pé : “ Ìwọ kò gbọ́dọ̀ ṣe panṣágà . ”
Olorun so o ninu Ofin ti o fun orile - ede Isireli pe : " Iwo ko gbodo se pansaga . "
Ṣùgbọ́n , ibi tí ìpínlẹ̀ Florida ní orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà wà lóde òní ló ti bá ara rẹ̀ .
Sugbon , ibi ti ipinle Florida ni orile - ede Amerika wa lode oni lo ti ba ara re .
( a ) Ìgbà wo ni àsọtẹ́lẹ̀ tí Aísáyà sọ nípa Jerúsálẹ́mù ṣẹ ?
( a ) Igba wo ni asotele ti Aisaya so nipa Jerusalemu se ?
Nígbà àtijọ́ , àwọn èèyàn máa ń sin òrìṣà mẹ́ta pa pọ̀ .
Nigba atijo , awon eeyan maa n sin orisa meta pa po .
Ìbẹ̀rù àìfẹ́ ṣe àṣìṣe lè máà jẹ́ kó o ṣe àwọn nǹkan láṣeyọrí
Iberu aife se asise le maa je ko o se awon nnkan laseyori
Ẹ máa fi wọ́n kọ́ àwọn ọmọ yín, ẹ máa sọ̀rọ̀ nípa wọn bí ẹ bá jókòó nínú ilé, àti ní ojú ọ̀nà bí ẹ bá ń rìn lọ, bí ẹ bá sùn àti bí ẹ bá jí.
E maa fi won ko awon omo yin, e maa soro nipa won bi e ba jokoo ninu ile, ati ni oju ona bi e ba n rin lo, bi e ba sun ati bi e ba ji.
Bí èmi kò sì tí mọ̀ bí a tí ń se ìwàdìí nǹkan wọ̀nyí, mo bí i lere pé ṣe ó ń fẹ́ lọ sì Jerúsálémù, kí a sì ṣe ẹjọ́ nǹkan wọ̀nyí níbẹ̀
Bi emi ko si ti mo bi a ti n se iwadii nnkan wonyi, mo bi i lere pe se o n fe lo si Jerusalemu, ki a si se ejo nnkan wonyi nibe
Tó o bá gbàdúrà sí Jèhófà , Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ Bàbá gbogbo ẹ̀dá lò ń gbàdúrà sí yẹn .
To o ba gbadura si Jehofa , Eledaa to je Baba gbogbo eda lo n gbadura si yen .
Gan - an gẹ́gẹ́ bí Jèhófà ti ń “ ṣe ọ̀nà àbájáde ” fún wa kí a lè fara da ìdẹwò , bẹ́ẹ̀ náà ni yóò ṣe ọ̀nà àbájáde fún wa nígbà tá a bá dojú kọ àwọn wàhálà tó dà bí ẹ̀gún nínú ẹran ara wa . — 1 Kọ́ríńtì 10 : 13 .
Gan - an gege bi Jehofa ti n " se ona abajade " fun wa ki a le fara da idewo , bee naa ni yoo se ona abajade fun wa nigba ta a ba doju ko awon wahala to da bi egun ninu eran ara wa . -- 1 Korinti 10 : 13 .
Ojúlówó àǹfààní ló máa ń wá látinú mímọ̀ àti gbígbàgbọ́ pé Jèhófà yóò tipasẹ̀ Jésù ràn wá lọ́wọ́ .
Ojulowo anfaani lo maa n wa latinu mimo ati gbigbagbo pe Jehofa yoo tipase Jesu ran wa lowo .
[1] Ní ọdún 2018, ó ṣe àkọ́kọ́ eré Nollywood pẹ̀lú eré "Family" tí Lancelot Imasuen kọ́kọ́ ṣe adarí rẹ̀.
[1] Ni odun 2018, o se akoko ere Nollywood pelu ere "Family" ti Lancelot Imasuen koko se adari re.
Òun ni àkọ́bí mi , a sì mọwọ́ ara wa gan - an ni ; ọ̀pọ̀ nǹkan la máa ń ṣe pa pọ̀ .
Oun ni akobi mi , a si mowo ara wa gan - an ni ; opo nnkan la maa n se pa po .
“ ‘Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún ẹranko, ẹyẹ, gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi àti àwọn ẹ̀dá tí ó ń rìn lórí ilẹ̀.
“ ‘Awon wonyi ni ilana fun eranko, eye, gbogbo eda alaaye ti n gbe inu omi ati awon eda ti o n rin lori ile.
Ula bí: Ara, Hanieli ati Risia.
Ula bi: Ara, Hanieli ati Risia.
Àpẹẹrẹ pàtàkì kan tí Pọ́ọ̀lù jíròrò nínú lẹ́tà rẹ̀ ni ti Ábúráhámù , ọkùnrin tó ní ìgbàgbọ́ , tó gbé ayé kí Jèhófà tó fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní àkójọ òfin àti ní ọ̀pọ̀ ọdún ṣáájú kí Kristi tó ṣí àǹfààní láti jogún ìyè ti ọ̀run sílẹ̀ .
Apeere pataki kan ti Poolu jiroro ninu leta re ni ti Aburahamu , okunrin to ni igbagbo , to gbe aye ki Jehofa to fun awon omo Isireli ni akojo ofin ati ni opo odun saaju ki Kristi to si anfaani lati jogun iye ti orun sile .
Lọ sókè àti sódò àwọn òpó Jérúsálẹ́mù Wò yíká, kí o sì mọ̀, kí o sì wá kiri Bí o bá le è rí ẹnìkan, tí ó jẹ́ olóòótọ́ àti olódodo, N ó dárí jìn ìlú yìí
Lo soke ati sodo awon opo Jerusalemu Wo yika, ki o si mo, ki o si wa kiri Bi o ba le e ri enikan, ti o je oloooto ati olododo, N o dari jin ilu yii
Kí làwọn nǹkan tá a lè ṣe láti fi hàn pé à ń wádìí ohun tí àwa fúnra wa jẹ́ ?
Ki lawon nnkan ta a le se lati fi han pe a n wadii ohun ti awa funra wa je ?
Alàgbà kan tó ń gbé ní ìlú tí wàhálà náà ti bẹ̀rẹ̀ gan - an ṣàlàyé pé : “ Nǹkan bí ọjọ́ márùn - ún lẹ́yìn tí ìjà náà bẹ̀rẹ̀ ni a ti ṣètò fún iṣẹ́ ìwàásù , ní àárín ìlú àti lágbègbè rẹ̀ .
Alagba kan to n gbe ni ilu ti wahala naa ti bere gan - an salaye pe : “ Nnkan bi ojo marun - un leyin ti ija naa bere ni a ti seto fun ise iwaasu , ni aarin ilu ati lagbegbe re .
Ó dájú pé ojúṣe tó ń buyì kúnni , tó sì ṣe pàtàkì lèyí jẹ́ pẹ̀lú .
O daju pe ojuse to n buyi kunni , to si se pataki leyi je pelu .
samosi
samosi
Gbogbo àwọn tá a dárúkọ yìí ló mọ̀ dájú pé ẹ̀bùn àbínibí tàbí ohun ìní yòówù káwọn ní , tàbí ipò pàtàkì tó wù káwọn wà , iṣẹ́ ìsìn àwọn sí Ọlọ́run ló gbọ́dọ̀ ṣe pàtàkì sáwọn ju iṣẹ́ oúnjẹ òòjọ́ àwọn lọ .
Gbogbo awon ta a daruko yii lo mo daju pe ebun abinibi tabi ohun ini yoowu kawon ni , tabi ipo pataki to wu kawon wa , ise isin awon si Olorun lo gbodo se pataki sawon ju ise ounje oojo awon lo .
Ẹlẹ́rìí náà sọ pé : “ Mi ò fi bẹ́ẹ̀ rí i kó sunkún rí , àmọ́ ó sunkún lọ́jọ́ tá a jọ sọ̀rọ̀ yìí . ”
Elerii naa so pe : " Mi o fi bee ri i ko sunkun ri , amo o sunkun lojo ta a jo soro yii . "
Báwo la ṣe lè fàánú hàn bíi ti Jèhófà táwọn èèyàn bá ṣẹ̀ wá ?
Bawo la se le faanu han bii ti Jehofa tawon eeyan ba se wa ?
Bàbá mi ní tirẹ̀ , Frank How , jẹ́ ọkùnrin jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ , òun ló sì kọ́kọ́ gbógun ti Màmá nítorí ẹ̀sìn tó ń ṣe .
Baba mi ni tire , Frank How , je okunrin jeejee , oun lo si koko gbogun ti Mama nitori esin to n se .
Ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́,kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn.Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀.
E wo enubode re teyin tope,ki e si wo inu agbala re teyin tiyin.E dupe lowo re,ki e si maa yin oruko re.
Màá máa wá àwọn èèyàn lọ ní ìrọ̀lẹ́ o , àmọ́ mo gbọ́dọ̀ máa lọ sí àwọn ìpàdé pàtàkì kan ní ìrọ̀lẹ́ Tuesday àti ìrọ̀lẹ́ Thursday . ”
Maa maa wa awon eeyan lo ni irole o , amo mo gbodo maa lo si awon ipade pataki kan ni irole Tuesday ati irole Thursday . ”
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Ibeere Lati Owo Awon Onkawe
Kò ju oṣù mẹ́jọ lọ tó bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó fi di akéde aláìṣèrìbọmi , kò sì pẹ́ sí àkókò yẹn tó fi ṣèrìbọmi .
Ko ju osu mejo lo to bere ikekoo Bibeli to fi di akede alaiseribomi , ko si pe si akoko yen to fi seribomi .
Àmọ́ àjọ yìí kógbá sílé nígbà tí Ogun Àgbáyé Kejì bẹ̀rẹ̀ .
Amo ajo yii kogba sile nigba ti Ogun Agbaye Keji bere .
Ó sì sun ara ẹran àti awọ rẹ̀ ní ẹ̀yìn ibùdó.
O si sun ara eran ati awo re ni eyin ibudo.
Ó sì sọ ọ̀wọ̀n náà ní Misipa, nítorí ó wí pé, “Kí OLUWA ṣọ́ wa nígbà tí a bá pínyà lọ́dọ̀ ara wa.
O si so owon naa ni Misipa, nitori o wi pe, "Ki OLUWA so wa nigba ti a ba pinya lodo ara wa.
dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ kábíyèsí aláṣẹ
dupe pupo lowo kabiyesi alase
ilẹ̀ ìlérí, nínú àwọn ohun èyí tí mo n yọ̀; bẹ̃ni, èmi sì mọ̀ wí pé Olúwa yíò gba àwọn ọmọkùnrin mi kúrò ní ọwọ́ Lábánì, yíò sì tún mú wọn sọ̀kalẹ̀ sí ọ̀dọ̀ wa nínú ijù.
ile ileri, ninu awon ohun eyi ti mo n yo; beni, emi si mo wi pe Oluwa yio gba awon omokunrin mi kuro ni owo Labani, yio si tun mu won sokale si odo wa ninu iju.
Ọjà tí a fowó rà, owó la fi ńpa.
Oja ti a fowo ra, owo la fi npa.
Bí Caroline ṣe rí i pé ó dá òun lóhùn tẹ̀rín - tẹ̀yẹ , ló yáa sọ pé : “ Tóò , jẹ́ kí n ṣàlàyé ohun tí mo fẹ́ bá Ìyáàfin B — sọ . ”
Bi Caroline se ri i pe o da oun lohun terin - teye , lo yaa so pe : " Too , je ki n salaye ohun ti mo fe ba Iyaafin B -- so . "
Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tí Wọ́n Jẹ́ “ Àpẹẹrẹ Fún Agbo ”
Awon Oluso Aguntan Ti Won Je “ Apeere Fun Agbo ”
Bíbélì rọ̀ ọ́ pé : “ Tọ́ ọ wò , kí [ o ] sì rí i pé Jèhófà jẹ́ ẹni rere ; aláyọ̀ ni abarapá ọkùnrin tí ó sá di í . ” — Sáàmù 34 : 8 .
Bibeli ro o pe : " To o wo , ki [ o ] si ri i pe Jehofa je eni rere ; alayo ni abarapa okunrin ti o sa di i . " -- Saamu 34 : 8 .
Nǹkan bí ọgọ́rùn - ún kìlómítà lápá gúúsù Sáréfátì ni tọkọtaya kan tí wọ́n jẹ́ ọ̀làwọ́ ń gbé .
Nnkan bi ogorun - un kilomita lapa guusu Sarefati ni tokotaya kan ti won je olawo n gbe .
Bí ó ti jé̩ pé àfi tí àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí bá yé ènìyàn nìkan ni a fi lè ní àmús̩e̩ è̩jé̩ yìí ní kíkún,
Bi o ti je pe afi ti awon eto ati ominira wonyi ba ye eniyan nikan ni a fi le ni amuse eje yii ni kikun,
Gbogbo wa pátá ló yẹ ká máa fìtara kọrin sókè sí Jèhófà , yálà a jẹ́ ọmọdé , àgbàlagbà tàbí ẹni tuntun .
Gbogbo wa pata lo ye ka maa fitara korin soke si Jehofa , yala a je omode , agbalagba tabi eni tuntun .
Síbẹ̀ , Jèhófà mọrírì ẹ̀mí ìfara - ẹni - jìn tí wọ́n ní bí wọ́n ṣe ń sìn níbikíbi tí àìní bá wà . ​ — Sm .
Sibe , Jehofa moriri emi ifara - eni - jin ti won ni bi won se n sin nibikibi ti aini ba wa . -- Sm .
Lọ́nà wo ?
Lona wo ?
ṣólómónì
solomoni
àdùlámù
adulamu
Dájúdájú Olúwa ni Olùṣọ lorí
Dajudaju Oluwa ni Oluso lori
Ẹni tí kò rí ayé rí ní ńsọ pé kò sẹ́ni tó gbọ́n bí òun.
Eni ti ko ri aye ri ni nso pe ko seni to gbon bi oun.
“ Sísọ̀rọ̀ ní àkókò tí kò tọ́ dà bí ìgbà téèyàn sọ ọ̀rọ̀ burúkú sí ẹlòmíì . ” ​ — Sirppa .
" Sisoro ni akoko ti ko to da bi igba teeyan so oro buruku si elomii . " -- Sirppa .
Ni màmá mi bá ra ohun ìṣeré kan fún mi tó ṣe é tò pọ̀ , tó sì ṣe é tú palẹ̀ .
Ni mama mi ba ra ohun isere kan fun mi to se e to po , to si se e tu pale .
Àmọ́ , tí inú wa bá ń dùn sí Ọ̀rọ̀ Jèhófà , a ó kórìíra “ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ojú àti fífi àlùmọ́ọ́nì ìgbésí ayé ẹni hàn sóde lọ́nà ṣekárími . ”
Amo , ti inu wa ba n dun si Oro Jehofa , a o koriira " ifekufee ara ati ifekufee oju ati fifi alumooni igbesi aye eni han sode lona sekarimi . "
Judith , àbúrò mi obìnrin sì jẹ́ ọmọ ọdún méjì ààbọ̀ .
Judith , aburo mi obinrin si je omo odun meji aabo .
“ Àwọn àpọ́sítélì adárarégèé ” nínú ìjọ Kọ́ríńtì hu ìwà àìlọ́wọ̀ sí Pọ́ọ̀lù .
“ Awon apositeli adararegee ” ninu ijo Korinti hu iwa ailowo si Poolu .
Nítorí náà, nítorí yín, a óo ro Sioni bí oko, Jerusalẹmu yóo di àlàpà, ahoro tẹmpili yóo sì di igbó kìjikìji.Dafidi bá pàṣẹ fún Joabu, ati àwọn ọ̀gágun rẹ̀, tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀, ó ní, “Ẹ lọ sí gbogbo ẹ̀yà Israẹli, láti Dani títí dé Beeriṣeba, kí ẹ sì ka gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà níbẹ̀, kí n lè mọ iye wọn.”Àbọ̀ ejò kì í gbé isà.
Nitori naa, nitori yin, a oo ro Sioni bi oko, Jerusalemu yoo di alapa, ahoro tempili yoo si di igbo kijikiji.Dafidi ba pase fun Joabu, ati awon ogagun re, ti won wa pelu re, o ni, “E lo si gbogbo eya Israeli, lati Dani titi de Beeriseba, ki e si ka gbogbo awon eniyan ti won wa nibe, ki n le mo iye won.”Abo ejo ki i gbe isa.
Sún kẹẹrẹ fa kẹẹrẹ ọkọ
Sun keere fa keere oko
Ṣe ìtọ́jú wọn títí di ọjọ́ kẹrìnlá oṣù yìí nígbà tí gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli yóò pa ẹran náà ní àfẹ̀mọ́júmọ́.
Se itoju won titi di ojo kerinla osu yii nigba ti gbogbo ijo eniyan Israeli yoo pa eran naa ni afemojumo.
Lọ́nà wo ?
Lona wo ?
Jésù sọ fún Màtá pé : “ Ẹni tí ó bá ń lo ìgbàgbọ́ nínú mi , bí ó tilẹ̀ kú , yóò yè , àti olúkúlùkù ẹni tí ó wà láàyè , tí ó sì ń lo ìgbàgbọ́ nínú mi , kì yóò kú láé . ”
Jesu so fun Mata pe : " Eni ti o ba n lo igbagbo ninu mi , bi o tile ku , yoo ye , ati olukuluku eni ti o wa laaye , ti o si n lo igbagbo ninu mi , ki yoo ku lae . "
Àmọ́ o , ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ nǹkan ló jẹ́ pé kò sí ìtọ́ni kan pàtó nípa wọn nínú Bíbélì .
Amo o , opo repete nnkan lo je pe ko si itoni kan pato nipa won ninu Bibeli .
․ ․ ․ ․ ․
. . . . .
Ìyókù àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ka èyí sí ìwà àìṣòótọ́ , wọ́n kà á sí ìṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà .
Iyoku awon omo Isireli ka eyi si iwa aisooto , won ka a si isote si Jehofa .
Ẹlòmíì tó tún jẹ́ ìṣúra iyebíye ni ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Martin .
Elomii to tun je isura iyebiye ni okunrin kan to n je Martin .
“ Lọ́ọ̀tì yan gbogbo Àgbègbè Jọ́dánì fún ara rẹ̀ , Lọ́ọ̀tì sì ṣí ibùdó rẹ̀ lọ sí ìlà - oòrùn .
" Looti yan gbogbo Agbegbe Jodani fun ara re , Looti si si ibudo re lo si ila - oorun .
Oun náà lo ṣe ọ̀nà tí mo fi yọ lọ́wọ́ Ẹlẹ́gbára, níbi tí a ti ń sọ̀rọ̀, ó bèèrè ohun tí mo rò pé òun lè fi ràn mi lọ́wọ́ mo sì ròyìn ìyọnu tí mo ti bá pàdé fun un. Lẹ́yìn èyí, ó pe àbúrò rẹ ọkùnrin, nígbà tí ó dé, o wí fún un pé kí o lọ gbé ọkọ̀ wá kí ó tù mí kọjá sí apá kejì odo, wéré wọ́n ti mu ọkọ̀ dé, àti èmi àti oun sì rékojá sí òdì kejìo lápá ibi tí mo wà. Kí a tó bọ sí inú ọkọ̀ ó ti béèrè nípa Fìlásayépọ̀ nítorí ó wí pé ẹgbọ́n òun ni, bàbá rẹ̀ jẹ́ àbúrò bàbá òun àwọn méjéèjì wá jẹ́ àbúrò olókun tíí ṣe alákòóso omi. Ó ní bàbá òun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ayédùbúlẹ̀ ni ẹni t;i wọ́n bí bàbá Fìláswayépọ̀ ń gbé kiri. Ó wí fún mi pé ó yẹ kí a wa Filásayépọ̀ rí, nítorí bí a bá le ríi, iwin tíí ṣe alákòóso fìlà rẹ̀ yóò kó wa yọ. Nígbà tí a gúnlẹ̀ sí òdì kejì tán, ó wí pé kí àbúrò òun tó jẹ́ iwin wá Fìlásayépọ̀ wá nní ibikíbi tí ó bá ti lè rii. Wéré tí ó wí báyìí, ṣe ni àbúrò rẹ̀ rá mọ́ wa lójú, nígbà tí o sì fi máa tó ìsẹ́jú mẹ́ta ṣe ni mo rí i tí o ń fò bọ̀ lófurufú tí ó gbé fìlàsayépọ̀ lé èjìká, tí ó gbé e kalẹ̀ lọdọ wa. Ìgbà tí iwin yìí rí fìlásayépọ̀ wọ̀n yọ̀ mọ́ ara wọn, wọ́n sì kí ara wọn dáadáa. Lẹ́yìn náà ó ni ki filásayépọ̀ pe iwin inú fila rẹ̀ fun òun, onítọ̀ún sì ṣe bẹ́ẹ̀. Nígbà tí iwin náà dé, kò ga púpọ̀, o sì sanra o ni iké ńlá kan lẹ́yìn. Òun ati obìnrin yìí sọ̀rọ̀ sí ara wọn ní èdè tì n kò gbọ rí, lẹ́yìn náà ni iwin tii ṣe alákòóso filà yìí bẹ̀rẹ̀, tí o ní ki n jókòó lé òun lẹ́yìn, nígbà tí mo sì ṣe bẹ́ẹ̀, wéré ni mo bá ara mi ni ofuurfú tí o ń fò lọ pẹ̀lú mi. Àyà mi kọ́ já ṣùgbọ́n ó ni ki n dì mọ́ òun lẹ́yìnn dáadáa kì n má ba à já lulẹ̀ mo rọra dọ̀bálẹ̀ lé e lẹ́yìn mo di iké ẹ̀yìn rẹ̀ mú dáadáa. Iwin náà ni irun lára bi ti ẹranko gan-an ni, irun wọ̀nyí ni mo si di mọ́ pẹ̀lú iké ẹ̀yìn rẹ̀ tí kò jẹ́ kí n já ṣubú. Nígbà tí ó pẹ́ díẹ̀ ó gbé mi sọ̀kalẹ̀ sí ojú ọ̀nà Igbó Elégbèje, ó sì wí fún mi pé a ti kúró ní àgbègbè ibi tí Ẹlẹ́gbára máa ń dé, ṣùgbọ́n ó wí fún mi ki n má kúrò nibi tí òun gbé mi s’’i nítorí òun ń lọ máa gbé àwọn yòókù lọ́kọ́ọ̀kan wá.
Oun naa lo se ona ti mo fi yo lowo Elegbara, nibi ti a ti n soro, o beere ohun ti mo ro pe oun le fi ran mi lowo mo si royin iyonu ti mo ti ba pade fun un. Leyin eyi, o pe aburo re okunrin, nigba ti o de, o wi fun un pe ki o lo gbe oko wa ki o tu mi koja si apa keji odo, were won ti mu oko de, ati emi ati oun si rekoja si odi kejio lapa ibi ti mo wa. Ki a to bo si inu oko o ti beere nipa Filasayepo nitori o wi pe egbon oun ni, baba re je aburo baba oun awon mejeeji wa je aburo olokun tii se alakooso omi. O ni baba oun ti oruko re n je Ayedubule ni eni t;i won bi baba Filaswayepo n gbe kiri. O wi fun mi pe o ye ki a wa Filasayepo ri, nitori bi a ba le rii, iwin tii se alakooso fila re yoo ko wa yo. Nigba ti a gunle si odi keji tan, o wi pe ki aburo oun to je iwin wa Filasayepo wa nni ibikibi ti o ba ti le rii. Were ti o wi bayii, se ni aburo re ra mo wa loju, nigba ti o si fi maa to iseju meta se ni mo ri i ti o n fo bo lofurufu ti o gbe filasayepo le ejika, ti o gbe e kale lodo wa. Igba ti iwin yii ri filasayepo won yo mo ara won, won si ki ara won daadaa. Leyin naa o ni ki filasayepo pe iwin inu fila re fun oun, onitoun si se bee. Nigba ti iwin naa de, ko ga pupo, o si sanra o ni ike nla kan leyin. Oun ati obinrin yii soro si ara won ni ede ti n ko gbo ri, leyin naa ni iwin tii se alakooso fila yii bere, ti o ni ki n jokoo le oun leyin, nigba ti mo si se bee, were ni mo ba ara mi ni ofuurfu ti o n fo lo pelu mi. Aya mi ko ja sugbon o ni ki n di mo oun leyinn daadaa ki n ma ba a ja lule mo rora dobale le e leyin mo di ike eyin re mu daadaa. Iwin naa ni irun lara bi ti eranko gan-an ni, irun wonyi ni mo si di mo pelu ike eyin re ti ko je ki n ja subu. Nigba ti o pe die o gbe mi sokale si oju ona Igbo Elegbeje, o si wi fun mi pe a ti kuro ni agbegbe ibi ti Elegbara maa n de, sugbon o wi fun mi ki n ma kuro nibi ti oun gbe mi s''i nitori oun n lo maa gbe awon yooku lokookan wa.
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 15 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 15 ]