diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ṣé Jèhóáṣì ń bá a nìṣó láti máa fetí sí Jèhóádà ?
Se Jehoasi n ba a niso lati maa feti si Jehoada ?
ẹ̀nìyàn sọnà pẹ̀lú òdodo, wọn sì n
eniyan sona pelu ododo, won si n
Òô mà ní ọrọ púpọ o.
Oo ma ni oro pupo o.
Tí ẹ sì jẹ oúnjẹ ilẹ̀ náà, ẹ mú nínú rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ìgbésókè wá fún Olúwa
Ti e si je ounje ile naa, e mu ninu re gege bi ore igbesoke wa fun Oluwa
( Fi wé Máàkù 13 : 28 - 30 ; Lúùkù 21 : 30 - 32 . )
( Fi we Maaku 13 : 28 - 30 ; Luuku 21 : 30 - 32 . )
Lẹ́yìn náà ni olùbánisọ̀rọ̀ yìí wá jíròrò báwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà ṣe gba ọ̀pọ̀ ìmọ̀ nígbà tí wọ́n wà lẹ́nu ẹ̀kọ́ wọn ní ilé ẹ̀kọ́ Gílíádì ‘ kí wọ́n lè fi èrò orí mòye ní kíkún ohun tí ìbú àti gígùn àti gíga àti jíjìn òtítọ́ jẹ́ ’ gẹ́gẹ́ bí Éfésù 3 : 18 ṣe sọ .
Leyin naa ni olubanisoro yii wa jiroro bawon akekoo naa se gba opo imo nigba ti won wa lenu eko won ni ile eko Giliadi ' ki won le fi ero ori moye ni kikun ohun ti ibu ati gigun ati giga ati jijin otito je ' gege bi Efesu 3 : 18 se so .
Kí ọ̀rọ̀ ọgbọ́n lè máa tẹnu wa jáde , ìmọ̀ Ìwé Mímọ́ gbọ́dọ̀ dé inú ọkàn wa pẹ̀lú .
Ki oro ogbon le maa tenu wa jade , imo Iwe Mimo gbodo de inu okan wa pelu .
Ẹ̀mí Mímọ́ sì fún mi ní àṣẹ
Emi Mimo si fun mi ni ase
Ká sọ pé kò fọwọ́ tó le tóyẹn mú iṣẹ́ yẹn ni ì bá má lè mú ẹ̀sìn Báálì kúrò ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì . ”
Ka so pe ko fowo to le toyen mu ise yen ni i ba ma le mu esin Baali kuro ni ile Isireli . ”
Ẹni tí ó ní ọwọ́ mímọ́ àti àyà funfun,ẹni tí kò gbé ọkàn rẹ̀ sókè sí asántí kò sì búra èké.
Eni ti o ni owo mimo ati aya funfun,eni ti ko gbe okan re soke si asanti ko si bura eke.
wọn dáko sori ilẹ̀ náà, bẹẹ̀ ni wọn
won dako sori ile naa, bee ni won
rì:
ri:
Nǹkan mìíràn tún wà tí ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù kọ́ wa .
Nnkan miiran tun wa ti oro Poolu ko wa .
Ní báyìí tó sì ti tó ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ààbọ̀ [ 3,500 ] ọdún sẹ́yìn tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé , kí la lè rí kọ́ látinú ojú táwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi wo “ ọwọ̀n iná àti àwọsánmà náà ” ? — Ẹ́kís .
Ni bayii to si ti to egberun meta aabo [ 3,500 ] odun seyin ti isele naa ti waye , ki la le ri ko latinu oju tawon omo Isireli fi wo " owon ina ati awosanma naa " ? -- Ekis .
Bí mo ṣe máa kẹ́kọ̀ọ́ yege níléèwé ló ká èmi lára ní tèmi , orin kíkọ tún ni ohun kejì tó gbà mí lọ́kàn .
Bi mo se maa kekoo yege nileewe lo ka emi lara ni temi , orin kiko tun ni ohun keji to gba mi lokan .
Àmọ́ , ṣé ọ̀pọ̀ jù lọ èèyàn máa fara balẹ̀ gbé ọ̀ràn tó fa yánpọnyánrin tàbí ìforígbárí náà yẹ̀ wò dáadáa ?
Amo , se opo ju lo eeyan maa fara bale gbe oran to fa yanponyanrin tabi iforigbari naa ye wo daadaa ?
Àwọn ọlọ́dẹ àtàwọn apẹja kan máa ń pa àwọn ẹranko láti fi dára yá .
Awon olode atawon apeja kan maa n pa awon eranko lati fi dara ya .
Látàrí ohun tá a ti jíròrò yìí , ó ṣe kedere pé ọ̀rọ̀ Jèhófà tó wà ní Aísáyà orí karùndínláàádọ́rin kì í ṣe ìlérí tí kò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀ .
Latari ohun ta a ti jiroro yii , o se kedere pe oro Jehofa to wa ni Aisaya ori karundinlaaadorin ki i se ileri ti ko lese nle .
Wọ́n sẹ́ àjọṣe tó wà láàárín Bàbá àti Ọmọ nípa ẹ̀kọ́ Mẹ́talọ́kan wọn .
Won se ajose to wa laaarin Baba ati Omo nipa eko Metalokan won .
Bí ìwọ bá ṣe bẹ́ẹ̀, bí wọn bá ké pè mi. Èmi yóò sì gbọ́ ohùn igbe wọn.
Bi iwo ba se bee, bi won ba ke pe mi. Emi yoo si gbo ohun igbe won.
Àwọn àpilẹ̀kọ yìí tí jẹ́ ká rí ohun tí kò jẹ́ kí Bíbélì pa run .
Awon apileko yii ti je ka ri ohun ti ko je ki Bibeli pa run .
Bíbélì ò pẹ́ ọ̀rọ̀ sọ rárá nígbà tó sọ pé : “ Gbogbo ènìyàn ti ṣẹ̀ , wọ́n sì ti kùnà láti kúnjú ìwọ̀n ògo Ọlọ́run . ” — Róòmù 3 : 23 .
Bibeli o pe oro so rara nigba to so pe : “ Gbogbo eniyan ti se , won si ti kuna lati kunju iwon ogo Olorun . ” — Roomu 3 : 23 .
Fún ìrànwọ́ láti lè fara da ìbànújẹ́ , wo ojú ìwé 14 - 19 nínú ìwé pẹlẹbẹ náà , Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú , tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tẹ̀ jáde .
Fun iranwo lati le fara da ibanuje , wo oju iwe 14 - 19 ninu iwe pelebe naa , Nigba Ti Enikan Ti Iwo Feran Ba Ku , ti awon Elerii Jehofa te jade .
Ògo tí ìwọ ti fi fún mi ni èmi sì ti fi fún wọn
Ogo ti iwo ti fi fun mi ni emi si ti fi fun won
Agbẹnusọ fún Àjọ Àwọn Ọ̀gá Iléèwé Nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ni a gbọ́ tó sọ pé : “ Ohun táwọn aráàlú ń sọ ni pé ‘ Ẹ̀tọ́ mi ni , ’ dípò ‘ Ojúṣe mi ni . ’ ”
Agbenuso fun Ajo Awon Oga Ileewe Nile Geesi ni a gbo to so pe : “ Ohun tawon araalu n so ni pe ‘ Eto mi ni , ’ dipo ‘ Ojuse mi ni . ’ ”
Ríran Àwọn Opó Lọ́wọ́ Nínú Gbogbo Àdánwò Wọn
Riran Awon Opo Lowo Ninu Gbogbo Adanwo Won
Pẹpẹ náà ṣàpẹẹrẹ bí Ọlọ́run ṣe múra tán láti tẹ́wọ́ gba ẹbọ tí Jésù fi ìwàláàyè rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá èèyàn rú .
Pepe naa sapeere bi Olorun se mura tan lati tewo gba ebo ti Jesu fi iwalaaye re gege bi eda eeyan ru .
Ó wá di dandan ká fi ilẹ̀ Potogí sílẹ̀ .
O wa di dandan ka fi ile Potogi sile .
Ko ronu pe o hun ṣe pataki, ati pe o jẹri si idagba ati ounjẹ ti Awọn ile-iṣẹ Ẹda.
Ko ronu pe o hun se pataki, ati pe o jeri si idagba ati ounje ti Awon ile-ise Eda.
Àwọn ẹ̀mí burúkú ti mọ̀ pé nǹkan awo sábà máa ń jọni lójú , torí náà wọ́n máa ń dọ́gbọ́n lò ó láti fi dẹkùn mú àwọn èèyàn kí wọ́n má ṣe jọ́sìn Jèhófà .
Awon emi buruku ti mo pe nnkan awo saba maa n joni loju , tori naa won maa n dogbon lo o lati fi dekun mu awon eeyan ki won ma se josin Jehofa .
Bẹ́ẹ̀ ni o , máa fi ìtara “ fọ́n oúnjẹ rẹ ” sí ojú omi púpọ̀ , kí o sì máa fi ẹ̀mí ọ̀làwọ́ “ fún irúgbìn rẹ , ” bíi ti Pọ́ọ̀lù , Jésù àtàwọn Ẹlẹ́rìí òde òní tí ń bẹ ní àgbègbè àwọn elédè Gẹ̀ẹ́sì ní Mẹ́síkò .
Bee ni o , maa fi itara " fon ounje re " si oju omi pupo , ki o si maa fi emi olawo " fun irugbin re , " bii ti Poolu , Jesu atawon Elerii ode oni ti n be ni agbegbe awon elede Geesi ni Mesiko .
Irú ojú wo tiẹ̀ ni Ọlọ́run fi ń wo àwọn nǹkan tó máa ń ṣẹlẹ̀ lágbo ijó alẹ́ táwọn ọ̀dọ́ ń lọ lóde òní ?
Iru oju wo tie ni Olorun fi n wo awon nnkan to maa n sele lagbo ijo ale tawon odo n lo lode oni ?
Kò sí òjé olóòrùn dídùn ní Gílíádì bí
Ko si oje oloorun didun ni Giliadi bi
“ Ènìyàn ti jọba lórí ènìyàn sí ìṣeléṣe rẹ̀ . ”
" Eniyan ti joba lori eniyan si iselese re . "
Ṣàlàyé . ( b ) Àwọn wo la fọkàn tán tí wọ́n sì yẹ lẹ́ni tá à ń sòótọ́ fún ?
Salaye . ( b ) Awon wo la fokan tan ti won si ye leni ta a n sooto fun ?
ọ̀rọ̀-ajé ètò ibánisọ̀rọ̀ àṣà yorùbá
oro-aje eto ibanisoro asa yoruba
Báwo la ṣe lè borí ẹ̀mí ìráhùn ?
Bawo la se le bori emi irahun ?
Nígbà tí àwọn ìjòyè Juda gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, wọ́n lọ sí ilé OLUWA láti ààfin ọba, wọ́n sì jókòó ní Ẹnu Ọ̀nà Titun tí ó wà ní ilé OLUWA.
Nigba ti awon ijoye Juda gbo oro yii, won lo si ile OLUWA lati aafin oba, won si jokoo ni Enu Ona Titun ti o wa ni ile OLUWA.
Ìwà ibi kún inú ayé yìí , àwọn ìjọba èèyàn sì ń kùnà láti pèsè àwọn ohun tó jẹ́ kòṣeémáàní fún àwọn aráàlú .
Iwa ibi kun inu aye yii , awon ijoba eeyan si n kuna lati pese awon ohun to je koseemaani fun awon araalu .
ayọ́lẹ̀wò
ayolewo
Juliana bojú wò mí , ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ orin náà pẹ̀lú mi !
Juliana boju wo mi , o si bere si i ko orin naa pelu mi !
Àṣeyọrí tó ń ṣe yẹn máa ń múnú rẹ̀ dùn , ìyẹn sì máa ń mú kí ọkàn rẹ̀ balẹ̀ láti máa ṣe nǹkan tó bá fẹ́ ṣe .
Aseyori to n se yen maa n munu re dun , iyen si maa n mu ki okan re bale lati maa se nnkan to ba fe se .
okerè
okere
Ẹ̀mí mímọ́ wá tipa bẹ́ẹ̀ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ , ó mú kó ṣe kedere sí Pétérù pé ohun tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rí yìí jẹ́ ìmúṣẹ àsọtẹ́lẹ̀ ìgbàanì kan .
Emi mimo wa tipa bee sise gege bi oluko , o mu ko se kedere si Peteru pe ohun ti awon omo eyin ri yii je imuse asotele igbaani kan .
Kí ni ohun àkọ́kọ́ tí ọ̀dọ́ kan tí ó ṣi ẹsẹ̀ gbé ní láti ṣe láti tún àjọṣe àárín òun àti Jèhófà ṣe , báwo sì ni àwọn òbí ṣe lè ran ọmọ náà lọ́wọ́ láti gbé ìgbésẹ̀ yẹn ?
Ki ni ohun akoko ti odo kan ti o si ese gbe ni lati se lati tun ajose aarin oun ati Jehofa se , bawo si ni awon obi se le ran omo naa lowo lati gbe igbese yen ?
Yóò tún ọkàn wọn rà padà lọ́wọ́ ìnilára àti lọ́wọ́ ìwà ipá . ”
Yoo tun okan won ra pada lowo inilara ati lowo iwa ipa . ”
olorin
olorin
Àwọn ọmọ ogun àwọn ọ̀tá jáde láti inú ìlú láti bá àwọn ọmọ ogun Joabu jà. Wọ́n pa ninu àwọn ọ̀gágun Dafidi, wọ́n sì pa Uraya ará Hiti náà.
Awon omo ogun awon ota jade lati inu ilu lati ba awon omo ogun Joabu ja. Won pa ninu awon ogagun Dafidi, won si pa Uraya ara Hiti naa.
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ìgbà táwọn kan lára wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ di onígbàgbọ́ ló ti mọ̀ wọ́n .
O see se ko je pe igba tawon kan lara won sese di onigbagbo lo ti mo won .
Dájúdájú nǹkan tẹ̀mí lè máyọ̀ kúnnú rẹ .
Dajudaju nnkan temi le mayo kunnu re .
Inú bí Mọ́mì ẹ gan -⁠ an .
Inu bi Momi e gan - an .
pé: 'Emi yòò fi àwọn (aláìgbọràn)
pe: 'Emi yoo fi awon (alaigboran)
54. Fir'aona sì rán àwọn akígbe
54. Fir'aona si ran awon akigbe
Ṣùgbọ́n ẹni tó bá ti pé ọmọ àádọ́ta ọdún gbọdọ̀ ṣíwọ́ nínú iṣẹ́ ojoojúmọ́ wọn nínú àgọ́, kí wọ́n sì má ṣiṣẹ́ mọ́
Sugbon eni to ba ti pe omo aadota odun gbodo siwo ninu ise ojoojumo won ninu ago, ki won si ma sise mo
Ó ní , “ Bá a bá ní èdèkòyédè , ńṣe ló máa ń tì mí dà nù , tí màá sì fara pa . ”
O ni , " Ba a ba ni edekoyede , nse lo maa n ti mi da nu , ti maa si fara pa . "
Nítorí àwọn ìdí kan , kò ṣeé ṣe fún gbogbo àwọn Júù láti rin ìrìn - àjò gígùn yẹn padà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà .
Nitori awon idi kan , ko see se fun gbogbo awon Juu lati rin irin - ajo gigun yen pada si Jerusalemu ati Juda .
Láìka èrò ọ̀pọ̀ èèyàn sí , àwọn ọmọ máa ń tẹ̀ lé ohun táwọn òbí wọn bá sọ ju bí wọ́n ṣe ń máa ń tẹ̀ lé táwọn ojúgbà wọn .
Laika ero opo eeyan si , awon omo maa n te le ohun tawon obi won ba so ju bi won se n maa n te le tawon ojugba won .
Ó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Jésè nípasẹ̀ Dáfídì tó jẹ́ ọmọ Jésè .
O je atomodomo Jese nipase Dafidi to je omo Jese .
Iṣẹ́ ìwàásù wa wà lára ohun tí Jèhófà pèsè káwọn tí òùngbẹ òtítọ́ ń gbẹ lè rí ìyè .
Ise iwaasu wa wa lara ohun ti Jehofa pese kawon ti oungbe otito n gbe le ri iye .
Àwọn kan máa ń sọ pé : “ Ẹ ò nílò ètò kankan táá máa darí yín .
Awon kan maa n so pe : “ E o nilo eto kankan taa maa dari yin .
Ní àsẹ̀yìnwá àsẹ̀yìnbọ̀ , a dá ìjọ kékeré elédè Spanish sílẹ̀ níbẹ̀ .
Ni aseyinwa aseyinbo , a da ijo kekere elede Spanish sile nibe .
Báwo làwọn ìtàn inú Bíbélì nípa àwọn onírera ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ ?
Bawo lawon itan inu Bibeli nipa awon onirera se le ran wa lowo ?
Bá a ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀ ni pé ká máa fetí sí àṣẹ Ọlọ́run .
Ba a se le se bee ni pe ka maa feti si ase Olorun .
Consider Ramón , the young man quoted earlier who cringed at the thought of identifying himself as a Christian at school .
Consider Ramon , the young man quoted earlier who cringed at the thought of identifying himself as a Christian at school .
Nígbà tó o ṣì kéré , ṣé ẹnì kan wà tọ́kàn ẹ ṣáà ń fà mọ́ ṣáá ?
Nigba to o si kere , se eni kan wa tokan e saa n fa mo saa ?
kí ó lè sinmi lọ́wọ́ ọjọ́ ìṣòro,títí tí a ó fi gbẹ́ kòtò fún eniyan burúkú.
ki o le sinmi lowo ojo isoro,titi ti a o fi gbe koto fun eniyan buruku.
gítaímù
gitaimu
N óo fi iṣan bò yín lára; lẹ́yìn náà n óo fi ara ẹran bò yín, n óo sì da awọ bò yín lára. N óo wá fi èémí si yín ninu, ẹ óo di alààyè, ẹ óo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA.’ ”
N oo fi isan bo yin lara; leyin naa n oo fi ara eran bo yin, n oo si da awo bo yin lara. N oo wa fi eemi si yin ninu, e oo di alaaye, e oo si mo pe emi ni OLUWA.' "
Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ lẹ́yin èyí, ọ̀pọ̀ nínú wọn ni kò ṣe ìgbọ́ràn sí Ọlọ́run
Sibesibe leyin eyi, opo ninu won ni ko se igboran si Olorun
imúwòdu
imuwodu
fún mi láti kọ wọ́n; emí sì ti kọ wọ́n. O sì paṣẹ fún mi pé ki èmi ó dì wọn ní èdìdí; ò sì tún ti pàṣẹ pé kí èmi ó dì itumọ̀ rẹ̀ ní èdìdí; nítorí eyi ni èmi ṣe dì àwọn atúmọ̀ ní èdìdí, gẹ́gẹ́bí àṣẹ Olúwa.
fun mi lati ko won; emi si ti ko won. O si pase fun mi pe ki emi o di won ni edidi; o si tun ti pase pe ki emi o di itumo re ni edidi; nitori eyi ni emi se di awon atumo ni edidi, gegebi ase Oluwa.
Gẹ́gẹ́ bó ti máa ń rí lára ọ̀pọ̀ èèyàn , Deborah ronú pé kò sóhun tó ṣe òun , nípa bẹ́ẹ̀ kò ṣe nǹkan kan sí àwọn àmì tó ń rí .
Gege bo ti maa n ri lara opo eeyan , Deborah ronu pe ko sohun to se oun , nipa bee ko se nnkan kan si awon ami to n ri .
lápapòọ yúòò máa bẹ lòrí wọn,
lapapoo yuoo maa be lori won,
Àmọ́ tó bá jẹ́ pé ibi pẹlẹbẹ kan náà ni ọ̀bẹ fi ń lélẹ̀ ńkọ́ ?
Amo to ba je pe ibi pelebe kan naa ni obe fi n lele nko ?
OLUWA ní, “Nisinsinyii, ẹ kíyèsí ohun tí yóo máa ṣẹlẹ̀ láti àkókò yìí lọ. Ẹ ranti bí ó ti rí fun yín kí ẹ tó fi ìpìlẹ̀ tẹmpili yìí lélẹ̀.
OLUWA ni, "Nisinsinyii, e kiyesi ohun ti yoo maa sele lati akoko yii lo. E ranti bi o ti ri fun yin ki e to fi ipile tempili yii lele.
Dídá Ẹ̀wù Àwọn Alufaa.
Dida Ewu Awon Alufaa.
Jésù lo okun Jèhófà láti ṣèrànwọ́ fún àwọn ẹlòmíràn
Jesu lo okun Jehofa lati seranwo fun awon elomiran
Ìsẹ̀lẹ̀ yìí fa iná àti ìrugùdù láti abẹ́ omi débi tí omi fi ru sókè tó mítà mẹ́ẹ̀ẹ́dógún , ìyẹn àádọ́ta ẹsẹ̀ bàtà , tó sì ya wọbẹ̀ wá láti Òkun Àtìláńtíìkì tó wà nítòsí ibẹ̀ .
Isele yii fa ina ati irugudu lati abe omi debi ti omi fi ru soke to mita meeedogun , iyen aadota ese bata , to si ya wobe wa lati Okun Atilantiiki to wa nitosi ibe .
Ìpayà rẹ̀ ò jẹ́ kọ́kàn èèyàn balẹ̀ ! ”
Ipaya re o je kokan eeyan bale ! "
Yóo jẹ́ ọjọ́ ìsinmi tí ó lọ́wọ̀, ẹ sì gbọdọ̀ gbààwẹ̀. Ọjọ́ ìsinmi náà yóo bẹ̀rẹ̀ láti ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹsan-an títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹwaa.”
Yoo je ojo isinmi ti o lowo, e si gbodo gbaawe. Ojo isinmi naa yoo bere lati irole ojo kesan-an titi di irole ojo kewaa.”
ó rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ nyín. Ṣùgbọ́n, ẹ kíyèsĩ, àyọrísí ọkàn tí ó sínwín ni èyí í ṣe; ìdàrúdàpọ̀ ọkàn nyín yĩ sì débá nyín nítorí àṣà àwọn bàbá nyin, èyítí ó jẹ́ kí ẹ̀yin ó gba àwọn ohun tí kĩ ṣe òtítọ́ gbọ́.
o ri idariji ese nyin. Sugbon, e kiyesi, ayorisi okan ti o sinwin ni eyi i se; idarudapo okan nyin yi si deba nyin nitori asa awon baba nyin, eyiti o je ki eyin o gba awon ohun ti ki se otito gbo.
reubẹni
reubeni
Ìtẹ̀síwájú ti ń bá a lọ láìsọsẹ̀ láti ìgbà yẹn wá .
Itesiwaju ti n ba a lo laisose lati igba yen wa .
Èrò Ṣọ́ọ̀lù ni wí pé kí Dáfídì ṣubú sí ọwọ́ àwọn ará Fílístínì
Ero Soolu ni wi pe ki Dafidi subu si owo awon ara Filistini
Báwo lo ṣe lè túbọ̀ rí ìgbádùn kíkọyọyọ nínú pípolongo Ìjọba náà ?
Bawo lo se le tubo ri igbadun kikoyoyo ninu pipolongo Ijoba naa ?
ojú ẹ̀Qnà tààrà.
oju eQna taara.
“Ọlọ́run wí pé, ‘Ní ìkẹyìn ọjọ́,Èmi yóò tú nínú Ẹ̀mí mí jáde sára ènìyàn gbogbo,àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti àwọn ọmọ yín obìnrin yóò máa sọtẹ́lẹ̀àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín yóò sì máa ríran,àwọn arúgbó yín yóò sì máa lá àlá;
“Olorun wi pe, ‘Ni ikeyin ojo,Emi yoo tu ninu Emi mi jade sara eniyan gbogbo,awon omo yin okunrin ati awon omo yin obinrin yoo maa soteleawon odomokunrin yin yoo si maa riran,awon arugbo yin yoo si maa la ala;
Nítorí ìdí yìí , Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run gbà wá nímọ̀ràn pé : “ Ẹ jẹ́ kí àsọjáde yín máa fìgbà gbogbo jẹ́ pẹ̀lú oore ọ̀fẹ́ , tí a fi iyọ̀ dùn , kí ẹ lè mọ bí ó ti yẹ kí ẹ fi ìdáhùn fún ẹnì kọ̀ọ̀kan . ”
Nitori idi yii , Oro Olorun gba wa nimoran pe : “ E je ki asojade yin maa figba gbogbo je pelu oore ofe , ti a fi iyo dun , ki e le mo bi o ti ye ki e fi idahun fun eni kookan . ”
Rò ó wò ná .
Ro o wo na .
Mààlúù kan ati aguntan mẹfa tí ó dára ni wọ́n ń bá mi pa lojumọ, wọn a tún máa bá mi pa ọpọlọpọ adìẹ. Ní ọjọ́ kẹwaa kẹwaa ni wọ́n máa ń tọ́jú ọpọlọpọ waini sinu awọ fún mi. Sibẹsibẹ, n kò bèèrè owó oúnjẹ tí ó jẹ́ ẹ̀tọ́ gomina, nítorí pé ara tí ń ni àwọn eniyan pupọ jù.
Maaluu kan ati aguntan mefa ti o dara ni won n ba mi pa lojumo, won a tun maa ba mi pa opolopo adie. Ni ojo kewaa kewaa ni won maa n toju opolopo waini sinu awo fun mi. Sibesibe, n ko beere owo ounje ti o je eto gomina, nitori pe ara ti n ni awon eniyan pupo ju.
Àyàfi bí àwọn ọmọ-ogunbá ṣẹ́ díẹ̀ kù fún wà,a ò bá ti rí bí Sodomu,a ò bá sì ti dàbí Gomorra.
Ayafi bi awon omo-ogunba se die ku fun wa,a o ba ti ri bi Sodomu,a o ba si ti dabi Gomorra.
Bí àpẹẹrẹ , ó yin ọ̀gá ẹgbẹ́ ọmọ ogun kan tí kì í ṣe Júù torí pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ tayọ .
Bi apeere , o yin oga egbe omo ogun kan ti ki i se Juu tori pe igbagbo re tayo .
Kí sì lẹ lè ṣe tí àlàáfíà fi máa jọba nínú ilé ?
Ki si le le se ti alaafia fi maa joba ninu ile ?
kaboni
kaboni
ílú; ìwọ, gbogbo Filistia, ti di yíyọ́; nítorí ẽfín yíò ti àríwá jáde wá, ẹnìkan kì yíò sì dá wà ní àkókò yíyàn rẹ̀.
ilu; iwo, gbogbo Filistia, ti di yiyo; nitori efin yio ti ariwa jade wa, enikan ki yio si da wa ni akoko yiyan re.
Ìgbìmọ̀ Olùṣekòkáárí
Igbimo Olusekokaari
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
NINU ITEJADE YII
dáadáa?
daadaa?
Ní ti tòótọ́ , ìwọ yóò sì fa wàrà àwọn orílẹ̀ - èdè mu , ìwọ yóò sì mu ọmú àwọn ọba ; dájúdájú , ìwọ yóò sì mọ̀ pé èmi , Jèhófà , ni Olùgbàlà rẹ . ”
Ni ti tooto , iwo yoo si fa wara awon orile - ede mu , iwo yoo si mu omu awon oba ; dajudaju , iwo yoo si mo pe emi , Jehofa , ni Olugbala re . "
Ìgbà tí a bá ní kí Ègùn má jà ní ńyọ̀bẹ.
Igba ti a ba ni ki Egun ma ja ni nyobe.