diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
tí ò n já ṣòòrò búra.
ti o n ja sooro bura.
77. Dájúdájú, ìbúra nla ni ẹ̀yí jẹ,
77. Dajudaju, ibura nla ni eyi je,
bi oô bá jẹ pé ẹ̀yin mò ni.
bi oo ba je pe eyin mo ni.
75. Dájúdájú ô. Jẹ. Al-kur'an
75. Dajudaju o. Je. Al-kur'an
Alápòọòn-ọnlé.
Alapooon-onle.
79. Ní inú Ìwé kan tí ô wà ní
79. Ni inu Iwe kan ti o wa ni
ìpamọ
ipamo
80. Éyí tí ẹnikẹni kò ní le fọwọ
80. Eyi ti enikeni ko ni le fowo
kàn àyàfi àwọn tí ô wà ní mímọ.
kan ayafi awon ti o wa ni mimo.
SI. Asọkalẹ̀ ni láti òdò Olúwa
SI. Asokale ni lati odo Oluwa
gbogbo ẹ̀dá.
gbogbo eda.
82. Ṣe irú ẹrọ yí ni ẹ̀yin yôòò kẹ?
82. Se iru ero yi ni eyin yooo ke?
83. Ẹ ha sọ pípé ẹrọ náà ní irọ di
83. E ha so pipe ero naa ni iro di
ìjẹ ati ìmu yín ni bí?
ije ati imu yin ni bi?
84. Béṣe nígbà náà, nígbà tí ẹ̀mí
84. Bese nigba naa, nigba ti emi
ẹni tí n pọká ikú bá dé ọnà ẹfun.
eni ti n poka iku ba de ona efun.
85. Tí ẹ̀yin ô sì máa wò sùn ùn.
85. Ti eyin o si maa wo sun un.
86. Nígbà náà Àwa sì súnmọ ọn
86. Nigba naa Awa si sunmo on
ju ẹ̀yin lọ ṣùgbọn ẹ kò ríran.
ju eyin lo sugbon e ko riran.
87. Kí ní ṣe nígbà náà ti 0 bá ṣe
87. Ki ni se nigba naa ti 0 ba se
pé ẹ kò ní jábọ iṣẹ yín?
pe e ko ni jabo ise yin?
88. Ẹ dá a padà (ẹ̀mí náà) bí ẹ̀yin
88. E da a pada (emi naa) bi eyin
bá jẹ olododo.
ba je olododo.
89. Bí òun (ẹni tí n kú lọ) bá jẹ
89. Bi oun (eni ti n ku lo) ba je
òkan. nínú: àwọn. olùsúnmọ
okan. ninu: awon. olusunmo
Ọlọrun.
Olorun.
90. Nígbà náà, ìtùnú, ìpẹ̀sẹ̀ àti
90. Nigba naa, itunu, ipese ati
Alijanna. onídẹ̀ra (yòò. wà. fún
Alijanna. onidera (yoo. wa. fun
Jobu tún dáhùn pé,“Kí ló dé tí o fi mú mi jáde láti inú ìyá mi?Ìbá sàn kí n ti kú,kí ẹnikẹ́ni tó rí mi.Bí ìròyìn yìí bá dé etí gomina, a óo bá a sọ̀rọ̀, kò ní sí ohunkohun tí yóo ṣẹ̀rù bà yín.”Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi, ọmọ Jese, ṣe jọba lórí gbogbo Israẹli. “Ṣe ìgbàyà ìdájọ́, èyí tí wọ́n ṣe iṣẹ́ ọnà dáradára sí lára, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọnà ara efodu náà: wúrà, aṣọ aláwọ̀ aró, aláwọ̀ elése àlùkò, aláwọ̀ pupa ati aṣọ ọ̀gbọ̀ tí ó ní ìlà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́, ni kí o fi ṣe é. Ṣugbọn ní tèmi, kí á má rí i pé mò ń fọ́nnu kiri àfi nítorí agbelebu Oluwa wa Jesu Kristi, nípasẹ̀ ẹni tí ayé yìí ti di ohun tí a kàn mọ́ agbelebu lójú mi, tí èmi náà sì di ẹni tí a kàn mọ́ agbelebu lójú rẹ̀. “Ọjọ́ ayé mi ti dópin, èrò ọkàn mi ti dàrú,àwọn ohun tí ọkàn mi ń fẹ́ sì ti di asán.Bí gbogbo ara bá jẹ́ ojú, báwo ni yóo ti ṣe gbọ́ràn? Bí gbogbo ara bá jẹ́ etí, báwo ni yóo ti ṣe gbóòórùn? “Dájúdájú OLUWA Ọlọrun kì í ṣe ohunkohun láì kọ́kọ́ fi han àwọn wolii, iranṣẹ rẹ̀.“Just so you won't find my hand empty” roasted popcorn for the masquerader; the masquerader also responded with “Just so you won't find my hands empty” and gave him a wooden doll.
Jobu tun dahun pe,“Ki lo de ti o fi mu mi jade lati inu iya mi?Iba san ki n ti ku,ki enikeni to ri mi.Bi iroyin yii ba de eti gomina, a oo ba a soro, ko ni si ohunkohun ti yoo seru ba yin.”Bee ni Dafidi, omo Jese, se joba lori gbogbo Israeli. “Se igbaya idajo, eyi ti won se ise ona daradara si lara, gege bi ise ona ara efodu naa: wura, aso alawo aro, alawo elese aluko, alawo pupa ati aso ogbo ti o ni ila teereteere, ni ki o fi se e. Sugbon ni temi, ki a ma ri i pe mo n fonnu kiri afi nitori agbelebu Oluwa wa Jesu Kristi, nipase eni ti aye yii ti di ohun ti a kan mo agbelebu loju mi, ti emi naa si di eni ti a kan mo agbelebu loju re. “Ojo aye mi ti dopin, ero okan mi ti daru,awon ohun ti okan mi n fe si ti di asan.Bi gbogbo ara ba je oju, bawo ni yoo ti se gboran? Bi gbogbo ara ba je eti, bawo ni yoo ti se gbooorun? “Dajudaju OLUWA Olorun ki i se ohunkohun lai koko fi han awon wolii, iranse re.“Just so you won't find my hand empty” roasted popcorn for the masquerader; the masquerader also responded with “Just so you won't find my hands empty” and gave him a wooden doll.
Ojú tì wọ́n pupọ wọn kò lè pada sílé. Nígbà tí Dafidi gbọ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wọn, ó ranṣẹ sí wọn pé kí wọ́n dúró sí Jẹriko títí tí irùngbọ̀n wọn yóo fi hù, lẹ́yìn náà kí wọ́n máa pada bọ̀ wá sílé.Ó dàbí igbó ṣúúrú ninu aṣálẹ̀,nǹkan rere kan kò lè ṣẹlẹ̀ sí i.Ninu ilẹ̀ gbígbẹ, ninu aṣálẹ̀ ni ó wà,ninu ilẹ̀ iyọ̀ tí ẹnikẹ́ni kò lè gbé.Bákan náà ni àwọn ẹlòmíràn dàbí irúgbìn tí a fún sórí òkúta, nígbà tí wọn bá gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọn á fi inú dídùn gbà á. Ọkunrin náà lọ sọ́dọ̀ ọmọ keji, ó sọ fún un bí ó ti sọ fún ekinni. Ọmọ náà dá a lóhùn pé, ‘Ó dára, mo gbọ́, Baba!’ Ṣugbọn kò lọ. Àwọn ọmọ Jafẹti ni Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki ati Tirasi. Bí a bá dákẹ́, tara ẹni a báni dákẹ́.
Oju ti won pupo won ko le pada sile. Nigba ti Dafidi gbo ohun ti o sele si won, o ranse si won pe ki won duro si Jeriko titi ti irungbon won yoo fi hu, leyin naa ki won maa pada bo wa sile.O dabi igbo suuru ninu asale,nnkan rere kan ko le sele si i.Ninu ile gbigbe, ninu asale ni o wa,ninu ile iyo ti enikeni ko le gbe.Bakan naa ni awon elomiran dabi irugbin ti a fun sori okuta, nigba ti won ba gbo oro naa, won a fi inu didun gba a. Okunrin naa lo sodo omo keji, o so fun un bi o ti so fun ekinni. Omo naa da a lohun pe, ‘O dara, mo gbo, Baba!’ Sugbon ko lo. Awon omo Jafeti ni Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meseki ati Tirasi. Bi a ba dake, tara eni a bani dake.
Nítorí Olórí Alufaa tí a ní kì í ṣe ẹni tí kò lè bá wa kẹ́dùn ninu àwọn àìlera wa. Ṣugbọn ó jẹ́ ẹni tí a ti dán wò ní gbogbo ọ̀nà bíi wa, ṣugbọn òun kò dẹ́ṣẹ̀. Èyí bí Eliṣa ninu, ó sì sọ fún ọba pé, “Bí ó bá jẹ́ pé o ta ọfà náà nígbà marun-un tabi mẹfa ni, ò bá ṣẹgun Siria patapata, ṣugbọn báyìí, ìgbà mẹta ni o óo ṣẹgun wọn.”Àbí ẹ kò mọ̀ pé ẹni tí ó bá alágbèrè lòpọ̀ ti di ara kan pẹlu rẹ̀? Ìwé Mímọ́ sọ pé. “Àwọn mejeeji yóo di ara kan.” Mose pẹlu Aaroni ati àwọn ọmọ wọn yóo pa àgọ́ tiwọn sí ìhà ìlà oòrùn, níwájú Àgọ́ Àjọ. Àwọn ni yóo máa ṣe iṣẹ́ ìsìn fún àwọn ọmọ Israẹli ní ibi mímọ́. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ ibi mímọ́, pípa ni kí wọ́n pa á. Nígbà tí Josẹfu jí láti ojú oorun, ó ṣe gẹ́gẹ́ bí angẹli Oluwa náà ti pàṣẹ fún un. Ó mú iyawo rẹ̀ sọ́dọ̀. Nítorí pé iṣẹ́ kan náà ni wọ́n ń ṣe, Paulu lọ wọ̀ lọ́dọ̀ wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́. Iṣẹ́ ọnà awọ tí wọ́n fi ń ṣe àgọ́ ni wọ́n ń ṣe. Ṣugbọn Dafidi jagun gba Sioni, ìlú olódi wọn. Sioni sì di ibi tí wọn ń pè ní ìlú Dafidi. Lẹ́yìn náà, wọ́n rú àwọn ẹbọ wọnyi: ẹbọ àtìgbà-dégbà, ẹbọ oṣù titun, gbogbo ẹbọ ọjọ́ àjọ̀dún tí a yà sọ́tọ̀ fún OLUWA, ati ti àwọn tí wọ́n bá fẹ́ rú ẹbọ àtinúwá sí OLUWA. Àtẹ́lẹwọ́ ẹni kì í tanni.
Nitori Olori Alufaa ti a ni ki i se eni ti ko le ba wa kedun ninu awon ailera wa. Sugbon o je eni ti a ti dan wo ni gbogbo ona bii wa, sugbon oun ko dese. Eyi bi Elisa ninu, o si so fun oba pe, “Bi o ba je pe o ta ofa naa nigba marun-un tabi mefa ni, o ba segun Siria patapata, sugbon bayii, igba meta ni o oo segun won.”Abi e ko mo pe eni ti o ba alagbere lopo ti di ara kan pelu re? Iwe Mimo so pe. “Awon mejeeji yoo di ara kan.” Mose pelu Aaroni ati awon omo won yoo pa ago tiwon si iha ila oorun, niwaju Ago Ajo. Awon ni yoo maa se ise isin fun awon omo Israeli ni ibi mimo. Enikeni ti o ba sunmo ibi mimo, pipa ni ki won pa a. Nigba ti Josefu ji lati oju oorun, o se gege bi angeli Oluwa naa ti pase fun un. O mu iyawo re sodo. Nitori pe ise kan naa ni won n se, Paulu lo wo lodo won, o si n sise. Ise ona awo ti won fi n se ago ni won n se. Sugbon Dafidi jagun gba Sioni, ilu olodi won. Sioni si di ibi ti won n pe ni ilu Dafidi. Leyin naa, won ru awon ebo wonyi: ebo atigba-degba, ebo osu titun, gbogbo ebo ojo ajodun ti a ya soto fun OLUWA, ati ti awon ti won ba fe ru ebo atinuwa si OLUWA. Atelewo eni ki i tanni.
Ẹ óo tún ṣe ọgbà àjàrà sórí òkè Samaria;àwọn tí wọ́n gbin àjàrà ni yóo sì gbádùn èso orí rẹ̀.Ojú tì mí láti gbà pé àwa kò lágbára tó láti hu irú ìwà bẹ́ẹ̀!Ṣugbọn bí ẹnìkan bá láyà láti fi ohun kan ṣe ìgbéraga, ẹ jẹ́ kí n sọ̀rọ̀ bí aṣiwèrè, èmi náà láyà láti ṣe ìgbéraga. Nítorí bí ẹ bá hùwà bí àwọn tí ẹran-ara ń darí, kíkú ni ẹ óo kú dandan. Ṣugbọn tí ẹ bá ń rìn lọ́nà ti Ẹ̀mí, tí ẹ kò sì hu ìwà ẹ̀ṣẹ̀ mọ́, ẹ óo yè. OLUWA tún fi ara hàn ní Ṣilo, nítorí pé níbẹ̀ ni ó ti kọ́ fi ara han Samuẹli, tí ó sì bá a sọ̀rọ̀.Ó ń sọ òkúta lu Dafidi ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn eniyan ńláńlá ati ọpọlọpọ eniyan mìíràn wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji Dafidi ọba. Ẹ máa gbé ìgbé-ayé yín pẹlu ọgbọ́n níwájú àwọn alaigbagbọ. Ẹ má ṣe jẹ́ kí àkókò kan kọjá láìjẹ́ pé ẹ lò ó bí ó ti yẹ. Ẹni tí bá ń ṣẹ́jú sí ni láti sọ̀rọ̀ èké, a máa dá ìjàngbọ̀n sílẹ̀,ṣugbọn ẹni tí bá ń báni wí ní gbangba, ń wá alaafia.Eyes are what see look on eyes and fill with kindness.
E oo tun se ogba ajara sori oke Samaria;awon ti won gbin ajara ni yoo si gbadun eso ori re.Oju ti mi lati gba pe awa ko lagbara to lati hu iru iwa bee!Sugbon bi enikan ba laya lati fi ohun kan se igberaga, e je ki n soro bi asiwere, emi naa laya lati se igberaga. Nitori bi e ba huwa bi awon ti eran-ara n dari, kiku ni e oo ku dandan. Sugbon ti e ba n rin lona ti Emi, ti e ko si hu iwa ese mo, e oo ye. OLUWA tun fi ara han ni Silo, nitori pe nibe ni o ti ko fi ara han Samueli, ti o si ba a soro.O n so okuta lu Dafidi ati gbogbo awon iranse re, bi o tile je pe awon eniyan nlanla ati opolopo eniyan miiran wa ni egbe kinni keji Dafidi oba. E maa gbe igbe-aye yin pelu ogbon niwaju awon alaigbagbo. E ma se je ki akoko kan koja laije pe e lo o bi o ti ye. Eni ti ba n seju si ni lati soro eke, a maa da ijangbon sile,sugbon eni ti ba n bani wi ni gbangba, n wa alaafia.Eyes are what see look on eyes and fill with kindness.
Àwọn ọmọ Iṣimaeli sì ń gbé ilẹ̀ tí ó bẹ̀rẹ̀ láti Hafila títí dé Ṣuri, tí ó wà ní òdìkejì Ijipti, ní apá Asiria. Wọ́n tẹ̀dó sí òdìkejì àwọn eniyan wọn.Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n pa, nítorí pé Ọlọrun ni ó jà fún wọn; wọ́n sì ń gbé ilẹ̀ àwọn ọ̀tá wọn títí tí àwọn ará Asiria fi kó wọn lẹ́rú.“Kabiyesi, Ọlọrun tí ó ga jùlọ fún Nebukadinesari, baba rẹ ní ìjọba, ó sọ ọ́ di ẹni ńlá, ó fún un ní ògo ati ọlá. Ṣugbọn bí wọn tí ń lọ, n óo da àwọ̀n lé wọn lórí, n óo mú wọn bí ẹyẹ ojú ọ̀run; n óo sì jẹ wọ́n níyà fún ìwà burúkú wọn.Bí ẹ bá wí pé, ‘Báwo ni a óo ṣe lépa rẹ̀!’Nítorí pé òun ló jẹ̀bi ọ̀rọ̀ yìí,“OLUWA ti fi ẹsẹ̀ tẹ àwọn akọni mi mọ́lẹ̀;ó pe ọpọlọpọ eniyan jọ sí mi,ó ní kí wọ́n pa àwọn ọdọmọkunrin mi;OLUWA ti tẹ àwọn ọmọ Juda ní àtẹ̀rẹ́,bí ẹni tẹ èso àjàrà fún ọtí waini.Jesu dá wọn lóhùn pé, “Èmi náà yóo bi yín léèrè ọ̀rọ̀ kan. Tí ẹ bá dá mi lóhùn, èmi náà yóo wá sọ irú agbára tí mo fi ń ṣe nǹkan wọnyi. Obinrin náà dáhùn pé, “Ta ni kí n pè fún ọ?” Saulu dáhùn pe, “Pe Samuẹli fún mi.”Sọ pé: 'Ta lẹni sọ Ìwé tí Musa
Awon omo Isimaeli si n gbe ile ti o bere lati Hafila titi de Suri, ti o wa ni odikeji Ijipti, ni apa Asiria. Won tedo si odikeji awon eniyan won.Opolopo eniyan ni won pa, nitori pe Olorun ni o ja fun won; won si n gbe ile awon ota won titi ti awon ara Asiria fi ko won leru.“Kabiyesi, Olorun ti o ga julo fun Nebukadinesari, baba re ni ijoba, o so o di eni nla, o fun un ni ogo ati ola. Sugbon bi won ti n lo, n oo da awon le won lori, n oo mu won bi eye oju orun; n oo si je won niya fun iwa buruku won.Bi e ba wi pe, ‘Bawo ni a oo se lepa re!’Nitori pe oun lo jebi oro yii,“OLUWA ti fi ese te awon akoni mi mole;o pe opolopo eniyan jo si mi,o ni ki won pa awon odomokunrin mi;OLUWA ti te awon omo Juda ni atere,bi eni te eso ajara fun oti waini.Jesu da won lohun pe, “Emi naa yoo bi yin leere oro kan. Ti e ba da mi lohun, emi naa yoo wa so iru agbara ti mo fi n se nnkan wonyi. Obinrin naa dahun pe, “Ta ni ki n pe fun o?” Saulu dahun pe, “Pe Samueli fun mi.”So pe: 'Ta leni so Iwe ti Musa
mú wá kalẹ̀, tí ô jẹ̀ ìmọlẹ̀ àti
mu wa kale, ti o je imole ati
ìtọsọnà fún àwọn bí o tilẹ̀
itosona fun awon bi o tile
Jẹ pé ẹ ṣe é ní abala ìwé lasan tí
Je pe e se e ni abala iwe lasan ti
ẹ fi han, tí ẹ sì fi ọpọlọpọ rẹ̀
e fi han, ti e si fi opolopo re
pamọ; tí A sì ti fi ohun tí ẹ kò mọ
pamo; ti A si ti fi ohun ti e ko mo
mò yin, ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín?-
mo yin, eyin ati awon baba yin?-
Sọ pé: 'Allah ni'. Lẹ̀hìn náà, fi
So pe: 'Allah ni'. Lehin naa, fi
wọn sílẹ̀ kí wọn máa dunra wọn
won sile ki won maa dunra won
nínú pẹ̀lú òrò (asán) wọn.
ninu pelu oro (asan) won.
93, Eyí sì j$ Ìwé kan tí Àwá tí
93, Eyi si j$ Iwe kan ti Awa ti
sòkalẹ̀ ti 0 kún fún ìbùkún, àti
sokale ti 0 kun fun ibukun, ati
lati mú òyí tô ti ṣíwajú rẹ̀ ṣẹ, kí ô
lati mu oyi to ti siwaju re se, ki o
tún lẹ̀ kìlọ fún Olú àwọn ìlú náà,
tun le kilo fun Olu awon ilu naa,
àti àwọn tô wà ní agbẹ̀gbe rẹ̀.
ati awon to wa ni agbegbe re.
Àwọn tí wọn gbàgbọ nínú ọjọ
Awon ti won gbagbo ninu ojo
ìkẹhìn gbàgbọ nínu rẹ̀, wọn sì n
ikehin gbagbo ninu re, won si n
ṣọ ìrun wọn.
so irun won.
94, Ta lo jẹ aláìṣẹ̀tọọ ju ẹni tí ô
94, Ta lo je alaisetoo ju eni ti o
dá àdapa irọ mọ Allah, tàbí tí ô n
da adapa iro mo Allah, tabi ti o n
sọ pé, 'A ti fi ìṣiípayá hàn mí,
so pe, 'A ti fi isiipaya han mi,
bẹ̀ ni A kò fi ìṣipayá kan kan
be ni A ko fi isipaya kan kan
hàn an; àti ẹni ti ô n sọ pé, "Emi
han an; ati eni ti o n so pe, "Emi
náà lẹ̀ sọ irú ohun tí Allah ti
naa le so iru ohun ti Allah ti
sòkalẹ̀?" Ìbá ṣe pé ìwọ lẹ̀ rí i ni,
sokale?" Iba se pe iwo le ri i ni,
nigbà tí àwọn alábòsí bá n
nigba ti awon alabosi ba n
pọkàkà ikú, tí àwọn Màláíkà sì n
pokaka iku, ti awon Malaika si n
na ọwọ wọn sí wọn (pé), 'ẹ ju
na owo won si won (pe), 'e ju
ẹ̀mi yín sílẹ̀. Lônìí yìí ni a ô fi ìyà
emi yin sile. Lonii yii ni a o fi iya
ìdòjútin!: san yín lẹsan, nítori
idojutin!: san yin lesan, nitori
ohun tí ẹ sọ sí Allah tí kì i ṣe
ohun ti e so si Allah ti ki i se
òtítọ, àti (nítorí pé) ẹ sí
otito, ati (nitori pe) e si
àwọn àmì Rẹ̀ pẹ̀lú ìyẹpẹrẹ."
awon ami Re pelu iyepere."
Ó fi ìṣákọ́lẹ̀ náà jíṣẹ́ fún Egiloni, ọba ilẹ̀ Moabu. Egiloni yìí jẹ́ ẹni tí ó sanra rọ̀pọ̀tọ̀. Ó bukun wọn, ó mú kí wọn bí sí i lọpọlọpọ,kò sì jẹ́ kí ẹran ọ̀sìn wọ́n dínkù. Ṣugbọn Ẹ̀mí Mímọ́ gbé Stefanu, ó tẹ ojú mọ́ òkè ọ̀run, ó rí ògo Ọlọrun, ó tún rí Jesu tí ó dúró lọ́wọ́ ọ̀tún Ọlọrun. Ohun tí ọba ń bèèrè yìí le pupọ, kò sí ẹni tí ó lè ṣe é, àfi àwọn oriṣa, nítorí pé àwọn kì í ṣe ẹlẹ́ran ara.”Ó tẹ́ pẹpẹ sinu gbọ̀ngàn meji tí ó wà ninu tẹmpili, wọ́n sì ń bọ àwọn ìràwọ̀ ati gbogbo ohun tí ó wà lójú ọ̀run níbẹ̀. Bí ó ti ń súre fún wọn, bẹ́ẹ̀ ni ó ń gòkè lọ kúrò lọ́dọ̀ wọn, ni a bá fi gbé e lọ sí ọ̀run. Bí ẹnikẹ́ni bá pe ara rẹ̀ ní wolii, baba ati ìyá rẹ̀ tí ó bí i yóo wí fún un pé yóo kú, nítorí ó ń purọ́ ní orúkọ OLUWA. Bí ó bá sọ àsọtẹ́lẹ̀, baba ati ìyá rẹ̀ yóo gún un pa. Bí ẹnìkan bá fi iná jó eniyan, kí wọ́n fi iná jó òun náà, bí ẹnìkan bá ṣá eniyan lọ́gbẹ́, kí wọ́n ṣá òun náà lọ́gbẹ́, bí ẹnìkan bá na eniyan lẹ́gba, kí wọ́n na òun náà lẹ́gba. Ẹni tí ó bá fẹ́ràn ìjà fẹ́ràn ẹ̀ṣẹ̀,ẹni tí ó bá fẹ́ràn kí á máa fi owó ṣe àṣehàn ń wá ìparun.The strategy one adopts in acquiring a wife will not do with regard to money.
O fi isakole naa jise fun Egiloni, oba ile Moabu. Egiloni yii je eni ti o sanra ropoto. O bukun won, o mu ki won bi si i lopolopo,ko si je ki eran osin won dinku. Sugbon Emi Mimo gbe Stefanu, o te oju mo oke orun, o ri ogo Olorun, o tun ri Jesu ti o duro lowo otun Olorun. Ohun ti oba n beere yii le pupo, ko si eni ti o le se e, afi awon orisa, nitori pe awon ki i se eleran ara.”O te pepe sinu gbongan meji ti o wa ninu tempili, won si n bo awon irawo ati gbogbo ohun ti o wa loju orun nibe. Bi o ti n sure fun won, bee ni o n goke lo kuro lodo won, ni a ba fi gbe e lo si orun. Bi enikeni ba pe ara re ni wolii, baba ati iya re ti o bi i yoo wi fun un pe yoo ku, nitori o n puro ni oruko OLUWA. Bi o ba so asotele, baba ati iya re yoo gun un pa. Bi enikan ba fi ina jo eniyan, ki won fi ina jo oun naa, bi enikan ba sa eniyan logbe, ki won sa oun naa logbe, bi enikan ba na eniyan legba, ki won na oun naa legba. Eni ti o ba feran ija feran ese,eni ti o ba feran ki a maa fi owo se asehan n wa iparun.The strategy one adopts in acquiring a wife will not do with regard to money.
73. Àwọn ọmọge ẹlẹ̀yinjú ẹgẹ ti
73. Awon omoge eleyinju ege ti
a pamọ sí ààyẹ̀ ìtọjú.
a pamo si aaye itoju.
74. Nígbà náà, ẹ̀wo ni nínú oore
74. Nigba naa, ewo ni ninu oore
Olúwa ẹ̀yin méjẹéjì, ni ẹ fẹ pẹ̀ ní
Oluwa eyin mejeeji, ni e fe pe ni
irọ?
iro?
75. Ti òọòunìyàn tàbí àlùjànnú
75. Ti ooouniyan tabi alujannu
kankan kò fọwọ kàn wọn ri
kankan ko fowo kan won ri
ṣíwájú wọn.
siwaju won.
76. Nígbà náà, ẹ̀wo ni nínú oore
76. Nigba naa, ewo ni ninu oore
Olúwa ẹ̀yin méjẹ̀òjì, ni ẹ fẹ pò ní
Oluwa eyin mejeoji, ni e fe po ni
irọ?
iro?
77. Wọn yÒéòò rẹọgbọòkú: sôri
77. Won yOeoo reogbooku: sori
tìmùtìmù tí ô fi àwọ jọ ewé tútù
timutimu ti o fi awo jo ewe tutu
àti ilẹ̀ tí 0 rẹwà dáradára.
ati ile ti 0 rewa daradara.
785. Nígbà náà, òwo ni nínú oore
785. Nigba naa, owo ni ninu oore
Olúwa ẹ̀yin méjẹéjì, ni ẹ fẹ pẹ̀ ní
Oluwa eyin mejeeji, ni e fe pe ni
irọ?
iro?
79. Ìbùkún ni fún Orúkọ Olúwa
79. Ibukun ni fun Oruko Oluwa
rẹ, Ọgá Ogo àti Ọlá nlá.
re, Oga Ogo ati Ola nla.
Ṣugbọn angẹli OLUWA pè é láti òkè ọ̀run, ó ní, “Abrahamu! Abrahamu!” Abrahamu dáhùn, ó ní, “Èmi nìyí.”nígbà tí a sin yín ninu omi ìrìbọmi, tí ẹ tún jinde nípa igbagbọ pẹlu agbára Ọlọrun tí ó jí Kristi dìde ninu òkú. Ìgboyà tí a ní níwájú Ọlọrun nìyí, pé bí a bá bèèrè ohunkohun ní ọ̀nà tí ó fẹ́, yóo gbọ́ tiwa. Kí OLUWA máa ranti ẹ̀ṣẹ̀ wọn nígbà gbogbo,kí á má sì ranti ìran wọn mọ́ láyé. “OLUWA nawọ́ sílẹ̀ láti òkè wá, ó dì mí mú,ó fà mí jáde kúrò ninu omi jíjìn.Nígbà tí OLUWA pàṣẹ fún ọkunrin tí ó wọ aṣọ funfun náà pé kí ó mú iná láàrin àwọn àgbá tí ń yí, tí ó wà láàrin àwọn Kerubu, ọkunrin náà wọlé, ó lọ dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ àgbá náà. Àgbà tí yó tẹ̀ẹ́, bó fárí tán, a ní ó ku járá ẹnu.
Sugbon angeli OLUWA pe e lati oke orun, o ni, “Abrahamu! Abrahamu!” Abrahamu dahun, o ni, “Emi niyi.”nigba ti a sin yin ninu omi iribomi, ti e tun jinde nipa igbagbo pelu agbara Olorun ti o ji Kristi dide ninu oku. Igboya ti a ni niwaju Olorun niyi, pe bi a ba beere ohunkohun ni ona ti o fe, yoo gbo tiwa. Ki OLUWA maa ranti ese won nigba gbogbo,ki a ma si ranti iran won mo laye. “OLUWA nawo sile lati oke wa, o di mi mu,o fa mi jade kuro ninu omi jijin.Nigba ti OLUWA pase fun okunrin ti o wo aso funfun naa pe ki o mu ina laarin awon agba ti n yi, ti o wa laarin awon Kerubu, okunrin naa wole, o lo duro legbee agba naa. Agba ti yo tee, bo fari tan, a ni o ku jara enu.
Àwọn ni yóo máa ru àwọn aṣọ ìkélé tí a fi ṣe ibi mímọ́, ati Àgọ́ Àjọ pẹlu àwọn ìbòrí rẹ̀, ati awọ ewúrẹ́ tí ń dán tí wọn fi bò ó, ati aṣọ títa fún ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ. Nígbà tí Jesu wọ inú ilé Peteru, ó rí ìyá iyawo Peteru tí ibà dá dùbúlẹ̀. Goṣeni, Holoni, ati Gilo; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkanla.Bí a ó ti ṣe é ní ńfi ara-a rẹ̀ hàn.
Awon ni yoo maa ru awon aso ikele ti a fi se ibi mimo, ati Ago Ajo pelu awon ibori re, ati awo ewure ti n dan ti won fi bo o, ati aso tita fun enu ona Ago Ajo. Nigba ti Jesu wo inu ile Peteru, o ri iya iyawo Peteru ti iba da dubule. Goseni, Holoni, ati Gilo; gbogbo ilu ati ileto won je mokanla.Bi a o ti se e ni nfi ara-a re han.
Ẹ kí gbogbo àwọn aṣiwaju yín ati gbogbo àwọn onigbagbọ. Àwọn ará láti Itali ki yín.OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, Ó ní ọmọkunrin kan tí ń jẹ́ Saulu. Saulu yìí jẹ́ arẹwà ọkunrin. Láti èjìká rẹ̀ sókè ni ó fi ga ju ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ Israẹli lọ, ó sì lẹ́wà ju ẹnikẹ́ni ninu wọn lọ.Nítorí pé nígbà tí àwọn eniyan náà kó ara wọn jọ, ẹnikẹ́ni láti inú àwọn tí ń gbé ìlú Jabeṣi Gileadi kò sí níbẹ̀. àwọn àgbèrè, àwọn ọkunrin tí ó ń bá ọkunrin lòpọ̀, àwọn gbọ́mọgbọ́mọ, àwọn onírọ́, àwọn tí ó ń búra èké, ati àwọn tí ń ṣe àwọn nǹkan mìíràn tí ó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ó dára, Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ jẹ́ iranṣẹ mi, ó níláti tẹ̀lé mi. Níbi tí èmi alára bá wà, níbẹ̀ ni iranṣẹ mi yóo wà. Bí ẹnikẹ́ni bá jẹ́ iranṣẹ mi, Baba mi yóo dá a lọ́lá.”àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọn,tí wọ́n sì ń yangàn nítorí wọ́n ní ọrọ̀ pupọ?Àwọn pidánpidán náà ṣe bẹ́ẹ̀ pẹlu ọgbọ́n idán wọn, wọ́n mú kí ọ̀pọ̀lọ́ bo ilẹ̀ Ijipti.Judasi Iskariotu, ọ̀kan ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila, bá lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí alufaa, ó lọ fi Jesu lé wọn lọ́wọ́. Àwọn alufaa ni wọ́n tún Òkè Ẹnubodè Ẹṣin ṣe, olukuluku tún ibi tí ó kọjú sí ilé rẹ̀ ṣe.Nítorí Ọ̀dọ́ Aguntan tí ó wà láàrin ìtẹ́ náà ni yóo máa ṣe olùtọ́jú wọn, yóo máa dà wọ́n lọ síbi ìsun omi ìyè.Ọlọrun yóo wá nu gbogbo omijé kúrò ní ojú wọn.” Kí alufaa náà yẹ ọ̀gangan ibi tí àrùn náà wà lára ẹni náà wò. Bí irun ọ̀gangan ibẹ̀ bá di funfun, tí àrùn náà bá jẹ wọ inú ara ẹni náà lọ, tí ó jìn ju awọ ara rẹ̀ lọ, àrùn ẹ̀tẹ̀ ni. Nígbà tí alufaa bá yẹ̀ ẹ́ wò, kí ó pè é ní aláìmọ́. Èyí ni omi Meriba, nítorí níbẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli ti ṣe gbolohun asọ̀ pẹlu OLUWA, tí OLUWA sì fi ara rẹ̀ hàn wọ́n pé mímọ́ ni òun. Nígbà tí ó rí Ẹsita tí ó dúró ní ìta, inú rẹ̀ dùn sí i, ọba na ọ̀pá oyè tí ó wà ní ọwọ́ rẹ̀ sí i, Ẹsita sì na ọwọ́, ó fi kan ṣóńṣó ọ̀pá náà. 52. Àti pé tí A bá sì rán atẹ̀gùn
E ki gbogbo awon asiwaju yin ati gbogbo awon onigbagbo. Awon ara lati Itali ki yin.OLUWA tun ba mi soro, o ni, O ni omokunrin kan ti n je Saulu. Saulu yii je arewa okunrin. Lati ejika re soke ni o fi ga ju enikeni ninu awon omo Israeli lo, o si lewa ju enikeni ninu won lo.Nitori pe nigba ti awon eniyan naa ko ara won jo, enikeni lati inu awon ti n gbe ilu Jabesi Gileadi ko si nibe. awon agbere, awon okunrin ti o n ba okunrin lopo, awon gbomogbomo, awon oniro, awon ti o n bura eke, ati awon ti n se awon nnkan miiran ti o lodi si eko ti o dara, Bi enikeni ba fe je iranse mi, o nilati tele mi. Nibi ti emi alara ba wa, nibe ni iranse mi yoo wa. Bi enikeni ba je iranse mi, Baba mi yoo da a lola.”awon ti won gbekele oro won,ti won si n yangan nitori won ni oro pupo?Awon pidanpidan naa se bee pelu ogbon idan won, won mu ki opolo bo ile Ijipti.Judasi Iskariotu, okan ninu awon omo-eyin mejila, ba lo si odo awon olori alufaa, o lo fi Jesu le won lowo. Awon alufaa ni won tun Oke Enubode Esin se, olukuluku tun ibi ti o koju si ile re se.Nitori Odo Aguntan ti o wa laarin ite naa ni yoo maa se olutoju won, yoo maa da won lo sibi isun omi iye.Olorun yoo wa nu gbogbo omije kuro ni oju won.” Ki alufaa naa ye ogangan ibi ti arun naa wa lara eni naa wo. Bi irun ogangan ibe ba di funfun, ti arun naa ba je wo inu ara eni naa lo, ti o jin ju awo ara re lo, arun ete ni. Nigba ti alufaa ba ye e wo, ki o pe e ni alaimo. Eyi ni omi Meriba, nitori nibe ni awon omo Israeli ti se gbolohun aso pelu OLUWA, ti OLUWA si fi ara re han won pe mimo ni oun. Nigba ti o ri Esita ti o duro ni ita, inu re dun si i, oba na opa oye ti o wa ni owo re si i, Esita si na owo, o fi kan sonso opa naa. 52. Ati pe ti A ba si ran ategun
lile kan sí wọn, tí wọn sì rí i
lile kan si won, ti won si ri i
(àwọn ohun ọgbìn wọn) tí ô di
(awon ohun ogbin won) ti o di
pípọn, lẹhìn náà ni wọn yôòò padà
pipon, lehin naa ni won yooo pada
di aláìmoore.
di alaimoore.
53. Ìwọ kò lẹ̀ jẹ kí òkú gbọ ẹ̀rò, o
53. Iwo ko le je ki oku gbo ero, o
kò sì lẹ̀ jẹ kí adití gbọ ìpẹ̀ nígbà tí
ko si le je ki aditi gbo ipe nigba ti
wọỌn bá ti pẹ̀hìndà.
woOn ba ti pehinda.
54. Ìwọ kò lẹ̀ tọ àwọn afọjú sọnà
54. Iwo ko le to awon afoju sona
kúrò nínú ìṣìnà wọn, bẹ̀ẹ̀ ni o kò
kuro ninu isina won, bee ni o ko
lẹ̀ mú ẹnìkan gbọràn àyàfi àwọn
le mu enikan gboran ayafi awon
tô gba àwọn Àmì Wa gbọ tí wọn
to gba awon Ami Wa gbo ti won
sì ju ara wọn síjlẹ̀ (fún Allah).
si ju ara won sijle (fun Allah).