diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
fún àwọn olùṣebi, irúfẹ ìyà tí ô
fun awon olusebi, irufe iya ti o
wà fún àwọn ẹlẹgbẹ wọn àtIJỌ,
wa fun awon elegbe won atIJO,
nitori náà kí wọn má ṣe kán Mi
nitori naa ki won ma se kan Mi
lòjú.
loju.
61. Lẹ̀hìn náà, ẹ̀gbé ni fún àwọn
61. Lehin naa, egbe ni fun awon
tí o ṣe àìgbàgbọ ní ọjọ náà tí a ti
ti o se aigbagbo ni ojo naa ti a ti
ṣe ìlérí fún wọn.
se ileri fun won.
Kí ó máa gúnwà níwájú Ọlọrun títí lae;máa fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́ rẹ ṣọ́ ọ.Ṣugbọn Mẹlikisẹdẹki tí kì í ṣe ìran Abrahamu gba ìdámẹ́wàá lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì súre fún Abrahamu tí ó rí àwọn ìlérí Ọlọrun gbà. N óo máa fi ẹnu mi yin OLUWA gidigidi,àní, n óo máa yìn ín ní àwùjọ ọ̀pọ̀ eniyan.Ọ̀rọ̀ Aguri, ọmọ Jake ará Masa nìyí:Ọkunrin yìí sọ fún Itieli ati Ukali pé,Bí o ti ń wò ó, òkúta kan là, ó sì ré bọ́ láti òkè, ó bá ère náà ní ẹsẹ̀ mejeeji tí ó jẹ́ àdàlú irin ati amọ̀, mejeeji sì fọ́ túútúú. Ìlérí adìẹ, asán ni lójú àwòdì.
Ki o maa gunwa niwaju Olorun titi lae;maa fi ife re ti ki i ye, ati otito re so o.Sugbon Melikisedeki ti ki i se iran Abrahamu gba idamewaa lowo re, o si sure fun Abrahamu ti o ri awon ileri Olorun gba. N oo maa fi enu mi yin OLUWA gidigidi,ani, n oo maa yin in ni awujo opo eniyan.Oro Aguri, omo Jake ara Masa niyi:Okunrin yii so fun Itieli ati Ukali pe,Bi o ti n wo o, okuta kan la, o si re bo lati oke, o ba ere naa ni ese mejeeji ti o je adalu irin ati amo, mejeeji si fo tuutuu. Ileri adie, asan ni loju awodi.
Ọgbọ́n kì í jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n yára bínú,ògo rẹ̀ sì níláti fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ dá.OLUWA ti búra, kò sì ní yí ọkàn rẹ̀ pada, pé,“Alufaa ni ọ́ títí lae,nípasẹ̀ Mẹlikisẹdẹki.” Ohun tí mò ń sọ ni pé mo fẹ́ wà láàrin yín kí n baà lè ní ìwúrí nípa igbagbọ yín, kí ẹ̀yin náà ní ìwúrí nípa igbagbọ mi.Kí ló dé tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wa fi gbọ́ tí wọn ń sọ èdè abínibí rẹ̀? Àwọn ẹ̀mí èṣù náà bá bẹ Jesu pé, “Bí o óo bá lé wa jáde, lé wa lọ sinu agbo ẹlẹ́dẹ̀ ọ̀hún nnì.”The cat being away from home, the house becomes a domain for mice.
Ogbon ki i je ki ologbon yara binu,ogo re si nilati foju fo ese da.OLUWA ti bura, ko si ni yi okan re pada, pe,“Alufaa ni o titi lae,nipase Melikisedeki.” Ohun ti mo n so ni pe mo fe wa laarin yin ki n baa le ni iwuri nipa igbagbo yin, ki eyin naa ni iwuri nipa igbagbo mi.Ki lo de ti enikookan wa fi gbo ti won n so ede abinibi re? Awon emi esu naa ba be Jesu pe, “Bi o oo ba le wa jade, le wa lo sinu agbo elede ohun nni.”The cat being away from home, the house becomes a domain for mice.
Bí ẹnìkán ṣe ohun tí ẹnìkan ò ṣe rí, ojú-u rẹ̀ á rí ohun tí ẹnìkan ò rí rí.
Bi enikan se ohun ti enikan o se ri, oju-u re a ri ohun ti enikan o ri ri.
Jehoiada bá mú Joaṣi jáde, ó gbé adé lé e lórí, ó fún un ní ìwé òfin. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe fi Joaṣi jọba, Jehoiada alufaa ati àwọn ọmọ rẹ̀ sì fi àmì òróró yàn án lọ́ba. Gbogbo eniyan hó pé, “Kí ọba pẹ́.”“Tí ẹ bá yá ẹnìkejì yín ní nǹkankan, ẹ kò gbọdọ̀ wọ ilé rẹ̀ lọ láti wá ohun tí yóo fi dógò. Àwọn eniyan Juda sì fi Asaraya, ọmọ rẹ̀, jọba. Ẹni ọdún mẹrindinlogun ni, nígbà tí ó jọba. Agbada náà nípọn ní ìwọ̀n ìbú àtẹ́lẹwọ́ kan. Etí rẹ̀ dàbí etí ife omi, ó tẹ̀ ní àtẹ̀sóde bí ìsàlẹ̀ òdòdó lílì. Agbada náà lè gbà tó ẹgbaa (2,000) galọọnu omi.Oholibama, Ela, Pinoni, Ta ni Ọlọrun bí kò ṣe OLUWA?Ta sì ni àpáta ààbò bí kò ṣe Ọlọrun wa?Idà ni ó kù tí ẹ gbẹ́kẹ̀lé; ẹ̀ ń ṣe ohun ìríra, ẹ̀ ń bá iyawo ara yín lòpọ̀, ẹ sì rò pé ẹ óo jogún ilẹ̀ yìí?When emergencies number two, one concentrates on one.
Jehoiada ba mu Joasi jade, o gbe ade le e lori, o fun un ni iwe ofin. Bee ni won se fi Joasi joba, Jehoiada alufaa ati awon omo re si fi ami ororo yan an loba. Gbogbo eniyan ho pe, “Ki oba pe.”“Ti e ba ya enikeji yin ni nnkankan, e ko gbodo wo ile re lo lati wa ohun ti yoo fi dogo. Awon eniyan Juda si fi Asaraya, omo re, joba. Eni odun merindinlogun ni, nigba ti o joba. Agbada naa nipon ni iwon ibu atelewo kan. Eti re dabi eti ife omi, o te ni atesode bi isale ododo lili. Agbada naa le gba to egbaa (2,000) galoonu omi.Oholibama, Ela, Pinoni, Ta ni Olorun bi ko se OLUWA?Ta si ni apata aabo bi ko se Olorun wa?Ida ni o ku ti e gbekele; e n se ohun irira, e n ba iyawo ara yin lopo, e si ro pe e oo jogun ile yii?When emergencies number two, one concentrates on one.
Labani wí pé, “Òkítì yìí ni ohun ẹ̀rí láàrin èmi pẹlu rẹ lónìí.” Nítorí náà ó sọ ọ́ ní Galeedi. Wọn yóo ṣe nǹkan wọnyi nítorí wọn kò mọ Baba, wọn kò sì mọ̀ mí. Ní ọdún kẹtalelogun tí Joaṣi, ọmọ Ahasaya, jọba ní Juda ni Jehoahasi, ọmọ Jehu, jọba lórí Israẹli ní Samaria, ó jọba fún ọdún mẹtadinlogun. “Tí ẹ̀yin ọmọ Israẹli bá yá ara yín lówó, tabi oúnjẹ tabi ohunkohun, ẹ kò gbọdọ̀ gba èlé lórí rẹ̀. Person-who-stones-and-breaks-partridge's-eggs; the eyes find what the eyes seek.
Labani wi pe, “Okiti yii ni ohun eri laarin emi pelu re lonii.” Nitori naa o so o ni Galeedi. Won yoo se nnkan wonyi nitori won ko mo Baba, won ko si mo mi. Ni odun ketalelogun ti Joasi, omo Ahasaya, joba ni Juda ni Jehoahasi, omo Jehu, joba lori Israeli ni Samaria, o joba fun odun metadinlogun. “Ti eyin omo Israeli ba ya ara yin lowo, tabi ounje tabi ohunkohun, e ko gbodo gba ele lori re. Person-who-stones-and-breaks-partridge's-eggs; the eyes find what the eyes seek.
Ó wà ní àkọsílẹ̀ pé, “Nítorí rẹ a wà ninu ewu ikú lojoojumọ,wọ́n sì ṣe wá bí aguntan tí wọ́n fẹ́ lọ pa.”Eliudi bí Eleasari, Eleasari bí Matani, Matani bí Jakọbu. Ẹ ṣí sílẹ̀ gbayau, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn,ẹ wà ní ṣíṣí sílẹ̀, ẹ̀yin ìlẹ̀kùn ayérayé,kí Ọba ògo lè wọlé.Arọ ò nasẹ̀ kan dí ọ̀nà.
O wa ni akosile pe, “Nitori re a wa ninu ewu iku lojoojumo,won si se wa bi aguntan ti won fe lo pa.”Eliudi bi Eleasari, Eleasari bi Matani, Matani bi Jakobu. E si sile gbayau, eyin ilekun,e wa ni sisi sile, eyin ilekun ayeraye,ki Oba ogo le wole.Aro o nase kan di ona.
Nítorí pé a máa gba talaka tí ó bá ké pè é sílẹ̀;a sì máa gba àwọn tí ìyà ń jẹ sílẹ̀,ati àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́.Dùgbẹ̀-dùgbẹ̀ kì í fi ẹyin rẹ̀ sílẹ̀.
Nitori pe a maa gba talaka ti o ba ke pe e sile;a si maa gba awon ti iya n je sile,ati awon ti ko ni oluranlowo.Dugbe-dugbe ki i fi eyin re sile.
Wọ́n kọ ilé OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn sílẹ̀, wọ́n sì ń sin oriṣa Aṣera ati àwọn ère mìíràn. Nítorí ìwà burúkú yìí, inú bí OLUWA sí Juda ati Jerusalẹmu. ó ń sùn lálẹ́, ó ń jí ní òwúrọ̀, irúgbìn ń hù, ó ń dàgbà ní ọ̀nà tí ọkunrin náà kò mọ̀. Jẹ́ ọlọ́gbọ́n kí o sì ní ìmọ̀.Má gbàgbé, má sì kọ ọ̀rọ̀ sí mi lẹ́nu.Naomi bá gba ọmọ náà, ó tẹ́ ẹ sí àyà rẹ̀, ó sì di olùtọ́jú rẹ̀.Àwọn ẹṣin dúdú ń fa kẹ̀kẹ́ tiwọn lọ sí ìhà àríwá, àwọn ẹṣin funfun ń lọ sí ìhà ìwọ̀ oòrùn, àwọn tí wọ́n jẹ́ kàláńkìnní ń lọ sí ìhà gúsù. Fi ẹ̀wọ̀n wúrà mejeeji bọ inú òrùka mejeeji yìí. Oluwa mi, gbọ́ ohun tí èmi iranṣẹ rẹ fẹ́ sọ. Bí ó bá jẹ́ pé OLUWA ni ó gbé ọ dìde sí mi, kí ó gba ẹbọ ẹ̀bẹ̀, ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé eniyan ni, kí ègún OLUWA wá sórí olúwarẹ̀, nítorí wọ́n lé mi jáde, kí n má baà ní ìpín ninu ilẹ̀ ìní tí OLUWA fún àwọn eniyan rẹ̀. Wọ́n ń sọ fún mi pé kí n lọ máa bọ oriṣa. Ọlọrun mi, mo mọ̀ pé ò máa yẹ ọkàn wò, o sì ní inú dídùn sí òtítọ́; tọkàntọkàn mi ni mo fi mú gbogbo nǹkan wọnyi wá fún ọ, mo sì ti rí i bí àwọn eniyan rẹ ti fi tọkàntọkàn ati inú dídùn mú ọrẹ wọn wá fún ọ. Ill will “is the” medicine that ensures misfortune.
Won ko ile OLUWA Olorun awon baba won sile, won si n sin orisa Asera ati awon ere miiran. Nitori iwa buruku yii, inu bi OLUWA si Juda ati Jerusalemu. o n sun lale, o n ji ni owuro, irugbin n hu, o n dagba ni ona ti okunrin naa ko mo. Je ologbon ki o si ni imo.Ma gbagbe, ma si ko oro si mi lenu.Naomi ba gba omo naa, o te e si aya re, o si di olutoju re.Awon esin dudu n fa keke tiwon lo si iha ariwa, awon esin funfun n lo si iha iwo oorun, awon ti won je kalankinni n lo si iha gusu. Fi ewon wura mejeeji bo inu oruka mejeeji yii. Oluwa mi, gbo ohun ti emi iranse re fe so. Bi o ba je pe OLUWA ni o gbe o dide si mi, ki o gba ebo ebe, sugbon bi o ba je pe eniyan ni, ki egun OLUWA wa sori oluware, nitori won le mi jade, ki n ma baa ni ipin ninu ile ini ti OLUWA fun awon eniyan re. Won n so fun mi pe ki n lo maa bo orisa. Olorun mi, mo mo pe o maa ye okan wo, o si ni inu didun si otito; tokantokan mi ni mo fi mu gbogbo nnkan wonyi wa fun o, mo si ti ri i bi awon eniyan re ti fi tokantokan ati inu didun mu ore won wa fun o. Ill will “is the” medicine that ensures misfortune.
Bí ẹ̀yà ara kan bá ń jẹ ìrora, gbogbo àwọn ẹ̀yà yòókù níí máa bá a jẹ ìrora. Bí ara bá tu ẹ̀yà kan, gbogbo àwọn ẹ̀yà yòókù ni yóo máa bá a yọ̀.Nígbà tí àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin rí àwọn ohun ìyanu tí Jesu ṣe, tí wọ́n tún gbọ́ bí àwọn ọmọde ti ń kígbe ninu Tẹmpili pé, “Hosana fún Ọmọ Dafidi,” inú wọn ru. Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́ ti rí mi sá,àwọn tí mo nífẹ̀ẹ́ ti kẹ̀yìn sí mi.Beṣasari bá pàṣẹ, pé kí wọ́n gbé ẹ̀wù elése àlùkò, ti àwọn olóyè, wọ Daniẹli, kí wọ́n sì fi ẹ̀gbà wúrà sí i lọ́rùn. Wọ́n kéde ká gbogbo ìjọba pé Daniẹli ni igbá kẹta ní ìjọba. Pẹlu ọpọlọpọ irú òwe bẹ́ẹ̀ ni Jesu fi ń sọ̀rọ̀ ìyìn rere fún wọn, gẹ́gẹ́ bí òye wọn ti mọ láti lè gbọ́. Àwọn arakunrin wọn ní ìdílé wọn ni: Mikaeli, Meṣulamu, ati Ṣeba; Jorai, Jakani, Sia, ati Eberi, gbogbo wọn jẹ́ meje. Ní gbogbo ìgbà tí àwọn iranṣẹ wọnyi ń dúró pé kí ọba ṣílẹ̀kùn, Ehudu ti sá lọ, ó sì ti kọjá òkúta gbígbẹ́ tí ó wà lẹ́bàá Giligali, ó ti sá dé Seira. Lẹ́sẹ̀kan náà, Saulu ṣubú lulẹ̀ gbalaja, nítorí pé ohun ti Samuẹli sọ dẹ́rùbà á gidigidi, àárẹ̀ sì mú un nítorí pé, kò jẹun ní gbogbo ọ̀sán ati òru náà. Ọ̀rọ̀ ẹnu olódodo a máa ṣe ọpọlọpọ eniyan ní anfaani,ṣugbọn òmùgọ̀ eniyan a máa kú nítorí àìgbọ́n.Fi òkúta Urimu ati òkúta Tumimu sí ara ìgbàyà ìdájọ́, kí wọn kí ó sì máa wà ní oókan àyà Aaroni, nígbà tí ó bá lọ siwaju OLUWA. Bẹ́ẹ̀ ni Aaroni yóo ṣe máa ru ìdájọ́ àwọn ọmọ Israẹli sí oókan àyà rẹ̀, nígbà gbogbo níwájú OLUWA. Ní ọjọ́ kan, bí Jakọbu ti ń se ẹ̀bẹ lọ́wọ́ ni Esau ti oko ọdẹ dé, ebi sì ti fẹ́rẹ̀ pa á kú. The pigeon hides its own disgrace and goes ridiculing the chicken.
Bi eya ara kan ba n je irora, gbogbo awon eya yooku nii maa ba a je irora. Bi ara ba tu eya kan, gbogbo awon eya yooku ni yoo maa ba a yo.Nigba ti awon olori alufaa ati awon amofin ri awon ohun iyanu ti Jesu se, ti won tun gbo bi awon omode ti n kigbe ninu Tempili pe, “Hosana fun Omo Dafidi,” inu won ru. Gbogbo awon ore mi timotimo ti ri mi sa,awon ti mo nifee ti keyin si mi.Besasari ba pase, pe ki won gbe ewu elese aluko, ti awon oloye, wo Danieli, ki won si fi egba wura si i lorun. Won kede ka gbogbo ijoba pe Danieli ni igba keta ni ijoba. Pelu opolopo iru owe bee ni Jesu fi n soro iyin rere fun won, gege bi oye won ti mo lati le gbo. Awon arakunrin won ni idile won ni: Mikaeli, Mesulamu, ati Seba; Jorai, Jakani, Sia, ati Eberi, gbogbo won je meje. Ni gbogbo igba ti awon iranse wonyi n duro pe ki oba silekun, Ehudu ti sa lo, o si ti koja okuta gbigbe ti o wa lebaa Giligali, o ti sa de Seira. Lesekan naa, Saulu subu lule gbalaja, nitori pe ohun ti Samueli so deruba a gidigidi, aare si mu un nitori pe, ko jeun ni gbogbo osan ati oru naa. Oro enu olododo a maa se opolopo eniyan ni anfaani,sugbon omugo eniyan a maa ku nitori aigbon.Fi okuta Urimu ati okuta Tumimu si ara igbaya idajo, ki won ki o si maa wa ni ookan aya Aaroni, nigba ti o ba lo siwaju OLUWA. Bee ni Aaroni yoo se maa ru idajo awon omo Israeli si ookan aya re, nigba gbogbo niwaju OLUWA. Ni ojo kan, bi Jakobu ti n se ebe lowo ni Esau ti oko ode de, ebi si ti fere pa a ku. The pigeon hides its own disgrace and goes ridiculing the chicken.
Bí àpẹẹrẹ, òfin igbeyawo de abilekọ níwọ̀n ìgbà tí ọkọ rẹ̀ wà láàyè. Ṣugbọn bí ọkọ rẹ̀ bá kú, òfin tí ó de obinrin náà mọ́ ọkọ rẹ̀ kò ṣiṣẹ́ mọ́. Ẹ máa wo àwọn aláìsàn sàn. Kí ẹ sọ fún wọn pé, ‘Ìjọba Ọlọrun ti dé àrọ́wọ́tó yín.’ The egg-bearing spider never leaves its eggs behind.
Bi apeere, ofin igbeyawo de abileko niwon igba ti oko re wa laaye. Sugbon bi oko re ba ku, ofin ti o de obinrin naa mo oko re ko sise mo. E maa wo awon alaisan san. Ki e so fun won pe, ‘Ijoba Olorun ti de arowoto yin.’ The egg-bearing spider never leaves its eggs behind.
OLUWA tún wá, ó dúró níbẹ̀, ó pe Samuẹli bí ó ti pè é tẹ́lẹ̀, ó ní “Samuẹli! Samuẹli!”Samuẹli bá dáhùn pé, “Máa wí, OLUWA, iranṣẹ rẹ ń gbọ́.”Àwa náà rí i pé, títí di òní olónìí, gbogbo ẹ̀dá ayé ni wọ́n ń jẹ̀rora, tí wọ́n sì ń rọbí bí aboyún. Gẹ́gẹ́ bí òtítọ́ Kristi ti wà ninu mi, kò sí ohun tí yóo mú mi yipada ninu ohun tí mo fi ń ṣe ìgbéraga ní gbogbo agbègbè Akaya. Ṣugbọn nígbà tí o bá ń ṣe ìtọrẹ àánú, má tilẹ̀ jẹ́ kí ọwọ́ òsì rẹ mọ ohun tí ọwọ́ ọ̀tún rẹ ń ṣe; Àṣá ḿbá ẹyẹlé ṣeré, ẹyẹlé ńyọ̀; ẹyẹlé ńfikú ṣeré.
OLUWA tun wa, o duro nibe, o pe Samueli bi o ti pe e tele, o ni “Samueli! Samueli!”Samueli ba dahun pe, “Maa wi, OLUWA, iranse re n gbo.”Awa naa ri i pe, titi di oni olonii, gbogbo eda aye ni won n jerora, ti won si n robi bi aboyun. Gege bi otito Kristi ti wa ninu mi, ko si ohun ti yoo mu mi yipada ninu ohun ti mo fi n se igberaga ni gbogbo agbegbe Akaya. Sugbon nigba ti o ba n se itore aanu, ma tile je ki owo osi re mo ohun ti owo otun re n se; Asa mba eyele sere, eyele nyo; eyele nfiku sere.
Bí túlàsí bá di méjì, ọ̀kan là ḿmú.
Bi tulasi ba di meji, okan la mmu.
Kiriati Baali (tí wọn ń pè ní Kiriati Jearimu), ati Raba, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ meji.Òun ni ó yan ilẹ̀ ìní wa fún wa,èyí tí àwọn ọmọ Jakọbu, àyànfẹ́ rẹ̀, fi ń yangàn.Mo gbọ́ ìkérora àwọn ọmọ Israẹli tí àwọn ará Ijipti dì ní ìgbèkùn, mo sì ranti majẹmu mi. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bá lọ jí i; wọ́n ní, “Oluwa, gbà wá là, à ń ṣègbé lọ!”Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí á máa rú ẹbọ ìsìn sí Ọlọrun nígbà gbogbo nípasẹ̀ Jesu. Èyí ni ohun tí ó yẹ gbogbo ẹni tí ó bá ń jẹ́wọ́ orúkọ rẹ̀. Bí ológbò-ó bá ṣẹ̀ ńpa ẹmọ́, à mọ̀ pé ó máa lọ.
Kiriati Baali (ti won n pe ni Kiriati Jearimu), ati Raba, gbogbo ilu ati ileto won je meji.Oun ni o yan ile ini wa fun wa,eyi ti awon omo Jakobu, ayanfe re, fi n yangan.Mo gbo ikerora awon omo Israeli ti awon ara Ijipti di ni igbekun, mo si ranti majemu mi. Awon omo-eyin re ba lo ji i; won ni, “Oluwa, gba wa la, a n segbe lo!”Nitori naa, e je ki a maa ru ebo isin si Olorun nigba gbogbo nipase Jesu. Eyi ni ohun ti o ye gbogbo eni ti o ba n jewo oruko re. Bi ologbo-o ba se npa emo, a mo pe o maa lo.
Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó mọ́ lójú ara rẹ̀,ṣugbọn OLUWA ló rí ọkàn.“OLUWA, ò máa ṣe olóòótọ́ sí gbogbo àwọn tí wọ́n bá hu ìwà òtítọ́ sí ọ;ò sì máa fi ara rẹ hàn bí aláìlẹ́bi, fún gbogbo àwọn tí kò ní ẹ̀bi.Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ mẹrẹẹrin wà lábẹ́ àwọn ìtẹ́dìí yìí, àṣepọ̀ mọ́ ìtẹ́lẹ̀ ni wọ́n ṣe àwọn ọ̀pá inú àgbá kẹ̀kẹ́ náà. Gíga àgbá kẹ̀kẹ́ kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ igbọnwọ kan ààbọ̀. Wọn óo kó gbogbo àwọn ohun èlò rẹ̀ sórí rẹ̀, àwọn àwo turari, àmúga tí a fi ń mú ẹran, ọkọ́ tí a fi ń kó eérú, àwo kòtò ati gbogbo ohun èlò tí ó jẹ mọ́ pẹpẹ náà, wọn óo fi awọ ewúrẹ́ bò wọ́n, wọn óo sì ti ọ̀pá tí a fi ń gbé e bọ̀ ọ́. Lójú wọn, o dàbí olóhùn iyọ̀ tí ń kọrin ìfẹ́, tí ó sì mọ ohun èlò orin lò dáradára. Wọ́n ń gbọ́ ohun tí ò ń wí, ṣugbọn wọn kò ní ṣe é. Àìsí-ńlé ológbò, ilé dilé èkúté.
Gbogbo ona eniyan ni o mo loju ara re,sugbon OLUWA lo ri okan.“OLUWA, o maa se oloooto si gbogbo awon ti won ba hu iwa otito si o;o si maa fi ara re han bi alailebi, fun gbogbo awon ti ko ni ebi.Awon agba keke mereerin wa labe awon itedii yii, asepo mo itele ni won se awon opa inu agba keke naa. Giga agba keke kookan si je igbonwo kan aabo. Won oo ko gbogbo awon ohun elo re sori re, awon awo turari, amuga ti a fi n mu eran, oko ti a fi n ko eeru, awo koto ati gbogbo ohun elo ti o je mo pepe naa, won oo fi awo ewure bo won, won oo si ti opa ti a fi n gbe e bo o. Loju won, o dabi olohun iyo ti n korin ife, ti o si mo ohun elo orin lo daradara. Won n gbo ohun ti o n wi, sugbon won ko ni se e. Aisi-nle ologbo, ile dile ekute.
Iyawo Finehasi, ọmọ Eli, wà ninu oyún ní àkókò náà, ọjọ́ ìkúnlẹ̀ rẹ̀ sì ti súnmọ́ etílé. Nígbà tí ó gbọ́ pé wọ́n ti gbé àpótí Ọlọrun lọ, ati pé baba ọkọ rẹ̀ ati ọkọ rẹ̀ ti kú, lẹsẹkẹsẹ ni ó bẹ̀rẹ̀ sí rọbí, tí ó sì bímọ. 32. Dájúdájú Àwa ni A rán ìrú
Iyawo Finehasi, omo Eli, wa ninu oyun ni akoko naa, ojo ikunle re si ti sunmo etile. Nigba ti o gbo pe won ti gbe apoti Olorun lo, ati pe baba oko re ati oko re ti ku, lesekese ni o bere si robi, ti o si bimo. 32. Dajudaju Awa ni A ran iru
nlá kan ṣosọ sí wọn, nítorí náà
nla kan soso si won, nitori naa
wọn dà gẹgẹ bí igi gbígbẹ tí a fi
won da gege bi igi gbigbe ti a fi
di ọgbà.
di ogba.
33. Àti pé dájúdájú Àwá ti ṣe
33. Ati pe dajudaju Awa ti se
Al-Kur'an. náà ní ìrọọrùn fún
Al-Kur'an. naa ni iroorun fun
ìrántí, nì jẹ ẹni tí yòò ṣe àkíyẹ̀sí n
iranti, ni je eni ti yoo se akiyesi n
bẹ bí?
be bi?
34. Àwọn ìran Luut pe àwọn
34. Awon iran Luut pe awon
ìkìlò náà ní irọ.
ikilo naa ni iro.
35. A rọ òjò òkuta lé wọn lorí,
35. A ro ojo okuta le won lori,
àyàfi àwọn ẹ̀nìyàn. Luut tí A
ayafi awon eniyan. Luut ti A
gbàlà ní kùtùkùtù òwúrọ.
gbala ni kutukutu owuro.
36. Ìgbàlà náà j€ ojú rere àánú
36. Igbala naa j€ oju rere aanu
láti ẹdò Wa, báyìí ni Awa ti ṣe n
lati edo Wa, bayii ni Awa ti se n
ṣan olùmòore lẹ̀san.
san olumoore lesan.
37. Àti pé, dájúdájú òún ti kìlò
37. Ati pe, dajudaju oun ti kilo
fún wọn nípa ìyà Wa, ṣùgbọn
fun won nipa iya Wa, sugbon
wọn ṣiyẹ̀méjì sí ìkìlọ náà.
won siyemeji si ikilo naa.
38. Àti pé, dájúdájú, wọn fẹ láti
38. Ati pe, dajudaju, won fe lati
ṣẹrí rẹ̀ kúrò lọdọ àwọn àlejò rẹ̀.
seri re kuro lodo awon alejo re.
ṣùgbọn A fọ ojú wọn. Nitorí náà.
sugbon A fo oju won. Nitori naa.
ẹ tọ ìyà àti ìkìlọ MI wò.
e to iya ati ikilo MI wo.
39, Àti pé dájúdájú ìyà ayérayé
39, Ati pe dajudaju iya ayeraye
ni ô JÍ wọn ní kùtùkùtù òwúrọ.
ni o JI won ni kutukutu owuro.
40. Nítorí náà, ẹ tọ ìyà Mi Wò.
40. Nitori naa, e to iya Mi Wo.
41. Àti pé dájúdájú Àwa ti ṣe. Al-
41. Ati pe dajudaju Awa ti se. Al-
Kur'an náà ní ìrọrùn fún ìrántí, nì jẹ
Kur'an naa ni irorun fun iranti, ni je
ẹni tí yòò ṣe àkíyẹ̀sí n bẹ bí?
eni ti yoo se akiyesi n be bi?
ÌDÁ 3
IDA 3
42. Àti pe dájúdájú àwọn olukìlò dé
42. Ati pe dajudaju awon olukilo de
wá bá àwọn ẹ̀nìyàn Fir'aona.
wa ba awon eniyan Fir'aona.
Lẹ́yìn èyí, ọmọ obinrin opó yìí ṣàìsàn. Àìsàn náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ọmọ náà ṣàìsí. ẹni tí ó dá àwọn ìmọ́lẹ̀ ńlá, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.The pot that wishes to eat pepper (stew) will first endure a scalded bottom.
Leyin eyi, omo obinrin opo yii saisan. Aisan naa po tobee ti omo naa saisi. eni ti o da awon imole nla, nitori pe ife re ti ki i ye wa titi lae.The pot that wishes to eat pepper (stew) will first endure a scalded bottom.
A máa ka òmùgọ̀ pàápàá kún ọlọ́gbọ́n,bí ó bá pa ẹnu rẹ̀ mọ́,olóye ni àwọn eniyan yóo pè é,bí ó bá panu mọ́ tí kò sọ̀rọ̀.Ẹsẹ̀ mi kò ranlẹ̀ mọ́ nítorí ààwẹ̀ gbígbà,mo rù kan egungun.Lẹ́yìn náà, wọ́n wá sọ fún Abrahamu pé Milika ti bímọ fún Nahori arakunrin rẹ̀. Ó lè dàbí ẹni pé ọgbọ́n wà ninu àwọn nǹkan wọnyi fún ìsìn ti òde ara ati fún ìjẹra-ẹni-níyà ati fún ìkóra-ẹni-níjàánu. Ṣugbọn wọn kò ṣe anfaani rárá láti jẹ́ kí eniyan borí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ti ara.Ó ní, “Ẹni ìyìn ni Ọlọrun títí ayérayé,ẹni tí ó ní ọgbọ́n ati agbára.Ṣugbọn bí ẹnìkan bá mọ̀ọ́nmọ̀ bá ẹlòmíràn jà, tí ó sì fi ọgbọ́n àrékérekè pa á, bí irú ẹni bẹ́ẹ̀ bá sálọ sí ibi pẹpẹ mi, fífà ni kí ẹ fà á kúrò níbi pẹpẹ náà kí ẹ sì pa á.EE WAR
A maa ka omugo paapaa kun ologbon,bi o ba pa enu re mo,oloye ni awon eniyan yoo pe e,bi o ba panu mo ti ko soro.Ese mi ko ranle mo nitori aawe gbigba,mo ru kan egungun.Leyin naa, won wa so fun Abrahamu pe Milika ti bimo fun Nahori arakunrin re. O le dabi eni pe ogbon wa ninu awon nnkan wonyi fun isin ti ode ara ati fun ijera-eni-niya ati fun ikora-eni-nijaanu. Sugbon won ko se anfaani rara lati je ki eniyan bori ifekufee ti ara.O ni, “Eni iyin ni Olorun titi ayeraye,eni ti o ni ogbon ati agbara.Sugbon bi enikan ba moonmo ba elomiran ja, ti o si fi ogbon arekereke pa a, bi iru eni bee ba salo si ibi pepe mi, fifa ni ki e fa a kuro nibi pepe naa ki e si pa a.EE WAR
(A sọ ọ kalẹ̀
(A so o kale
1. Ní Orúkọ Allah Olôore òfẹ
1. Ni Oruko Allah Oloore ofe
Aláàánú jùlọ.
Alaaanu julo.
ni Olùrí ohun gbogbo)... Awọn
ni Oluri ohun gbogbo)... Awon
wọn yí jẹ ẹsẹ Iwé kan tí ô yanjú.
won yi je ese Iwe kan ti o yanju.
3. Dájúdájú Àwá sọ ALKur'an
3. Dajudaju Awa so ALKur'an
kalẹ̀ ní Larubawa ki ẹ lẹ̀ gbọ
kale ni Larubawa ki e le gbo
àgbọyé.
agboye.
4. Àwa n fún ọ ni ìròyìn tí ô dára
4. Awa n fun o ni iroyin ti o dara
Jùlọ, nipa pé A sọ AlKur'an yìí
Julo, nipa pe A so AlKur'an yii
kalẹ̀ fún ọ, bí oô tilẹ̀ Jẹ pé ṣíwájú
kale fun o, bi oo tile Je pe siwaju
rẹ̀, ìwọ ti Jẹ Ọkan nínú àwọn tí kò
re, iwo ti Je Okan ninu awon ti ko
mò (nípa rẹ̀).
mo (nipa re).
53. Nígbà tí Yusuf sọ fún bàbá rẹ̀
53. Nigba ti Yusuf so fun baba re
pé; 'Bàbá mi, mo rí àwọn ìràWỌ
pe; 'Baba mi, mo ri awon iraWO
mọkànlá, òòrùn àti òṣùpá. (lôjú
mokanla, oorun ati osupa. (loju
àlá) tí wọn n foríbalẹ̀ fún mi."
ala) ti won n foribale fun mi."
6. Ô wí pé, "Ìwọ ọmọ mi, má ṣe
6. O wi pe, "Iwo omo mi, ma se
rọ àlá rẹ fún àwọn arákùnrin rẹ kí
ro ala re fun awon arakunrin re ki
wọn ma baà d€te sí ọ; Dájúdájú
won ma baa d€te si o; Dajudaju
ẹ̀nìyàn.
eniyan.
7. Àti pé báyìí ni Olúwa rẹ̀ yôò
7. Ati pe bayii ni Oluwa re yoo
ṣà ọ lẹṣà, tí Òun yòò sì fi ìtumò
sa o lesa, ti Oun yoo si fi itumo
àwọn ọrọ mọ Ọ, tí yòò sì ṣe àṣepé
awon oro mo O, ti yoo si se asepe
ojú rere Rẹ̀ lé ọ lòrí, àti fún ìdílé
oju rere Re le o lori, ati fun idile
Yakuub gẹ̀gẹ bí Ò ti ṣe é ní àṣepé
Yakuub gege bi O ti se e ni asepe
fún àwọn baba-nla rẹ̀ tí 0 ṣíwájú,
fun awon baba-nla re ti 0 siwaju,
Ibrahimọ àti Is-haka. Dájúdájú
Ibrahimo ati Is-haka. Dajudaju
Kí ló ń jáde bọ̀ láti inú aṣálẹ̀ yìí,tí ó dàbí òpó èéfín,tí ó kún fún òórùn dídùn òjíá ati turari,pẹlu òórùn dídùn àtíkè àwọn oníṣòwò?Dafidi di idà Saulu mọ́ ihamọra náà, ó sì gbìyànjú láti rìn, ṣugbọn kò lè rìn nítorí pé kò wọ ihamọra ogun rí. Dafidi sọ fún Saulu pé, “N kò lè lo ihamọra yìí, nítorí pé n kò wọ̀ ọ́ rí.” Dafidi bá tú wọn kúrò lára rẹ̀. Tí a bá ṣe ìdájọ́ òtítọ́, inú olódodo a dùn,ṣugbọn ìfòyà ni fún àwọn aṣebi.Nígbà tí àwọn iranṣẹ Saulu dé láti mú Dafidi, Mikali sọ fún wọn pé, “Ara rẹ̀ kò yá.” Nítorí Kristi ti fi òpin sí Òfin láti mú gbogbo ẹni tí ó bá gbàgbọ́ rí ìdáláre níwájú Ọlọrun.“Arakunrin yóo fi arakunrin rẹ̀ fún ikú pa; baba yóo fi ọmọ rẹ̀ fún ikú pa. Àwọn ọmọ yóo gbógun ti àwọn òbí wọn, wọn yóo fi wọ́n fún ikú pa. Ogbó ti mú kí ojú Israẹli di bàìbàì ní àkókò yìí, kò sì ríran dáradára mọ́. Josẹfu bá kó wọn súnmọ́ baba rẹ̀, baba rẹ̀ dì mọ́ wọn, ó sì fi ẹnu kò wọ́n lẹ́nu. Dafidi wí fún un pé, “Má bẹ̀rù, oore ni mo fẹ́ ṣe ọ́ nítorí Jonatani baba rẹ. Gbogbo ilẹ̀ tí ó ti jẹ́ ti Saulu baba baba rẹ rí, ni n óo dá pada fún ọ, a óo sì jọ máa jẹun lórí tabili mi nígbà gbogbo.”“Ìwọ ọmọ eniyan, ohun tí èmi OLUWA Ọlọrun sọ nípa ilẹ̀ Israẹli ni pé: òpin ti dé. Òpin dé sórí igun mẹrẹẹrin ilẹ̀ náà.Ní òdìkejì odò Jọdani, ní apá ìlà oòrùn, ní ilẹ̀ Moabu, ni Mose ti ṣe àlàyé àwọn òfin wọnyi. Ó ní, Ọ̀nà rẹ̀ tura pupọ,alaafia sì ni gbogbo ọ̀nà rẹ̀.Tamari dáhùn pé, “Rárá, má fi ipá mú mi, nítorí ẹnìkan kò gbọdọ̀ dán irú rẹ̀ wò ní Israẹli, má hùwà òmùgọ̀; Kí kabiyesi yan àwọn alabojuto ní ilẹ̀ náà kí wọ́n kó ìdámárùn-ún ìkórè ilẹ̀ Ijipti jọ láàrin ọdún meje tí ọ̀pọ̀ oúnjẹ yóo fi wà. Ọdẹ a-fi-fìlà-pa-erin, ọjọ́ kan ni òkìkí-i ẹ̀ ḿmọ.
Ki lo n jade bo lati inu asale yii,ti o dabi opo eefin,ti o kun fun oorun didun ojia ati turari,pelu oorun didun atike awon onisowo?Dafidi di ida Saulu mo ihamora naa, o si gbiyanju lati rin, sugbon ko le rin nitori pe ko wo ihamora ogun ri. Dafidi so fun Saulu pe, “N ko le lo ihamora yii, nitori pe n ko wo o ri.” Dafidi ba tu won kuro lara re. Ti a ba se idajo otito, inu olododo a dun,sugbon ifoya ni fun awon asebi.Nigba ti awon iranse Saulu de lati mu Dafidi, Mikali so fun won pe, “Ara re ko ya.” Nitori Kristi ti fi opin si Ofin lati mu gbogbo eni ti o ba gbagbo ri idalare niwaju Olorun.“Arakunrin yoo fi arakunrin re fun iku pa; baba yoo fi omo re fun iku pa. Awon omo yoo gbogun ti awon obi won, won yoo fi won fun iku pa. Ogbo ti mu ki oju Israeli di baibai ni akoko yii, ko si riran daradara mo. Josefu ba ko won sunmo baba re, baba re di mo won, o si fi enu ko won lenu. Dafidi wi fun un pe, “Ma beru, oore ni mo fe se o nitori Jonatani baba re. Gbogbo ile ti o ti je ti Saulu baba baba re ri, ni n oo da pada fun o, a oo si jo maa jeun lori tabili mi nigba gbogbo.”“Iwo omo eniyan, ohun ti emi OLUWA Olorun so nipa ile Israeli ni pe: opin ti de. Opin de sori igun mereerin ile naa.Ni odikeji odo Jodani, ni apa ila oorun, ni ile Moabu, ni Mose ti se alaye awon ofin wonyi. O ni, Ona re tura pupo,alaafia si ni gbogbo ona re.Tamari dahun pe, “Rara, ma fi ipa mu mi, nitori enikan ko gbodo dan iru re wo ni Israeli, ma huwa omugo; Ki kabiyesi yan awon alabojuto ni ile naa ki won ko idamarun-un ikore ile Ijipti jo laarin odun meje ti opo ounje yoo fi wa. Ode a-fi-fila-pa-erin, ojo kan ni okiki-i e mmo.
Ọba sọ fún Ẹsita Ayaba pé, “Àwọn Juu ti pa ẹẹdẹgbẹta (500) ọkunrin ati àwọn ọmọ Hamani mẹ́wẹ̀ẹ̀wá ní Susa. Kí ni àwọn Juu tí wọ́n wà ní àwọn agbègbè ṣe? Nisinsinyii, kí ni ìbéèrè rẹ? A óo sì ṣe é fún ọ.”Àwọn ọmọ Lefi ni: Ṣemaaya, ọmọ Haṣubu, ọmọ Asirikamu, ọmọ Haṣabaya, ọmọ Bunni.Mose bá kọjú sí Kora, ó ní: “Ẹ gbọ́ ẹ̀yin ọmọ Lefi! Samuẹli dáhùn pé, “Alaafia ni. Ẹbọ ni mo wá rú sí OLUWA. Ẹ ya ara yín sí mímọ́ kí ẹ bá mi lọ síbi ìrúbọ náà.” Ó ya Jese ati àwọn ọmọ rẹ̀ sí mímọ́, ó sì pè wọ́n síbi ìrúbọ náà.Kò pẹ́ pupọ lẹ́yìn náà, ni Joabu ati àwọn ọmọ ogun Dafidi pada dé láti ibi tí wọ́n ti lọ ja ogun kan, wọ́n sì kó ọpọlọpọ ìkógun bọ̀. Ṣugbọn Abineri kò sí lọ́dọ̀ Dafidi, ní Heburoni, nígbà tí wọ́n dé, nítorí pé Dafidi ti ní kí ó máa pada lọ, ó sì ti lọ ní alaafia. Ó wà pẹlu Dafidi nígbà tí Dafidi bá àwọn ará Filistia jagun ní Pasi Damimu, wọ́n wà ninu oko ọkà baali kan nígbà tí àwọn ọmọ ogun Israẹli bẹ̀rẹ̀ sí sá fún àwọn ará Filistia. Balaamu sọ fún Balaki pé, “Tẹ́ pẹpẹ meje sí ibí yìí fún mi kí o sì pèsè akọ mààlúù meje ati àgbò meje.”Ṣugbọn OLUWA tún mú kí ọkàn Farao le, kò sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Israẹli lọ.Mo sì rí aadọrin ninu àwọn àgbààgbà àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n dúró níwájú àwọn oriṣa wọnyi, Jaasanaya ọmọ Ṣafani dúró láàrin wọn. Olukuluku mú ohun tí ó fi ń sun turari lọ́wọ́, èéfín turari sì ń fẹ́ lọ sókè. Nítorí Ọmọ-Eniyan pàápàá kò wá pé kí eniyan ṣe iranṣẹ fún un, ó wá láti ṣe iranṣẹ ni, ati láti fi ẹ̀mí rẹ̀ ṣe ìràpadà fún ọpọlọpọ eniyan.”Nígbà náà ni OLUWA fara han Abramu, ó wí pé, “Àwọn ọmọ ati ọmọ ọmọ rẹ ni n óo fi ilẹ̀ yìí fún.” Abramu bá tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ fún OLUWA tí ó fara hàn án. Lẹ́yìn tí Lọti ti kúrò lọ́dọ̀ Abramu, OLUWA sọ fún Abramu pé, “Gbé ojú rẹ sókè, kí o wò ó láti ibi tí o wà yìí, títí lọ sí ìhà àríwá ati sí ìhà gúsù, tún wò ó lọ sí ìhà ìlà oòrùn títí dé ìhà ìwọ̀ oòrùn. Ó ní, “Èmi ni OLUWA, mo ti pè ọ́ ninu òdodo, mo ti di ọwọ́ rẹ mú,mo sì pa ọ́ mọ́.Mo ti fi ọ́ ṣe majẹmu fún aráyé,mo sì fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè;88.. Àyàfi ìké-àánú láti. ẹ̀dọ
Oba so fun Esita Ayaba pe, “Awon Juu ti pa eedegbeta (500) okunrin ati awon omo Hamani meweewa ni Susa. Ki ni awon Juu ti won wa ni awon agbegbe se? Nisinsinyii, ki ni ibeere re? A oo si se e fun o.”Awon omo Lefi ni: Semaaya, omo Hasubu, omo Asirikamu, omo Hasabaya, omo Bunni.Mose ba koju si Kora, o ni: “E gbo eyin omo Lefi! Samueli dahun pe, “Alaafia ni. Ebo ni mo wa ru si OLUWA. E ya ara yin si mimo ki e ba mi lo sibi irubo naa.” O ya Jese ati awon omo re si mimo, o si pe won sibi irubo naa.Ko pe pupo leyin naa, ni Joabu ati awon omo ogun Dafidi pada de lati ibi ti won ti lo ja ogun kan, won si ko opolopo ikogun bo. Sugbon Abineri ko si lodo Dafidi, ni Heburoni, nigba ti won de, nitori pe Dafidi ti ni ki o maa pada lo, o si ti lo ni alaafia. O wa pelu Dafidi nigba ti Dafidi ba awon ara Filistia jagun ni Pasi Damimu, won wa ninu oko oka baali kan nigba ti awon omo ogun Israeli bere si sa fun awon ara Filistia. Balaamu so fun Balaki pe, “Te pepe meje si ibi yii fun mi ki o si pese ako maaluu meje ati agbo meje.”Sugbon OLUWA tun mu ki okan Farao le, ko si je ki awon omo Israeli lo.Mo si ri aadorin ninu awon agbaagba awon omo Israeli, won duro niwaju awon orisa wonyi, Jaasanaya omo Safani duro laarin won. Olukuluku mu ohun ti o fi n sun turari lowo, eefin turari si n fe lo soke. Nitori Omo-Eniyan paapaa ko wa pe ki eniyan se iranse fun un, o wa lati se iranse ni, ati lati fi emi re se irapada fun opolopo eniyan.”Nigba naa ni OLUWA fara han Abramu, o wi pe, “Awon omo ati omo omo re ni n oo fi ile yii fun.” Abramu ba te pepe kan nibe fun OLUWA ti o fara han an. Leyin ti Loti ti kuro lodo Abramu, OLUWA so fun Abramu pe, “Gbe oju re soke, ki o wo o lati ibi ti o wa yii, titi lo si iha ariwa ati si iha gusu, tun wo o lo si iha ila oorun titi de iha iwo oorun. O ni, “Emi ni OLUWA, mo ti pe o ninu ododo, mo ti di owo re mu,mo si pa o mo.Mo ti fi o se majemu fun araye,mo si fi o se imole awon orile-ede;88.. Ayafi ike-aanu lati. edo
Olúwa rẹ. Dájúdájú ojú rere Rẹ̀
Oluwa re. Dajudaju oju rere Re
fún ọ jẹ ohun tí ô tObi lòrí rẹ.
fun o je ohun ti o tObi lori re.
89. Sọ pé: 'Bí àwọn ẹ̀nìyàn àti
89. So pe: 'Bi awon eniyan ati
Alujannu bá tilẹ̀ pa ara wọn pọ
Alujannu ba tile pa ara won po
lati lò mú irú yìí wá,
lati lo mu iru yii wa,
wọn kò ní lẹ̀ mú irú rẹ̀ wá bi ô
won ko ni le mu iru re wa bi o
tilẹ̀ jẹ pé wọn n ran ara wọn
tile je pe won n ran ara won
lọwọ.
lowo.
90. Àti pé dájúdájú Àwa ti ṣe
90. Ati pe dajudaju Awa ti se
ẹ̀nìyàn. nínú. AlKur'an. yìí
eniyan. ninu. AlKur'an. yii
ṣùgbọn. ọpọlọpọ. àwọn. ẹ̀nìyàn
sugbon. opolopo. awon. eniyan
lòdì. sí ohun gbogbo àyàfi
lodi. si ohun gbogbo ayafi
àìgbàgbọ.
aigbagbo.
91. Wọn sì wí pé: 'A kò ní gbà ọ
91. Won si wi pe: 'A ko ni gba o
gbQ, títí tí ìwọ yôòò fi j$ kí omi
gbQ, titi ti iwo yooo fi j$ ki omi