diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
àwọn ọrun àti ayé; Allah jẹ Ọlọrọ,
awon orun ati aye; Allah je Oloro,
Ẹni tí ìyìn tọ sí.
Eni ti iyin to si.
133. Tí Allah ní ohun gbogbo tí n
133. Ti Allah ni ohun gbogbo ti n
bẹ nínú àwọn ọrun àti ayé. Allah sì
be ninu awon orun ati aye. Allah si
tô ní Aláàbò.
to ni Alaabo.
134. Bí ôbá wù Ú, Ò le mú yín kúrò,
134. Bi oba wu U, O le mu yin kuro,
ẹ̀yin ẹ̀nìyàn kí O sì fi àwọn mìíràn
eyin eniyan ki O si fi awon miiran
pààrọ yín. Allah sì jẹ Alágbára láti ṣe
paaro yin. Allah si je Alagbara lati se
ẹ̀yí.
eyi.
“Nítorí náà, sọ fún un pé, èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ní ‘mo mú un wá láti inú pápá, níbi tí ó ti ń da ẹran, pé kí ó wá jọba lórí, àwọn eniyan mi, Israẹli. Nítorí pé àwọn eniyan wọnyi ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n ti sọ ibí di aláìmọ́ pẹlu turari tí wọn ń sun sí àwọn oriṣa tí àwọn, ati àwọn baba wọn, ati àwọn ọba Juda kò mọ̀ rí. Wọ́n ti pa àwọn aláìṣẹ̀ sí gbogbo ibí yìí. Ṣé ìlú olókìkí yín náà nìyí,tí a ti tẹ̀dó láti ìgbà àtijọ́!Tí ó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ rìn lọ sí ilẹ̀ òkèèrè,tí ó ṣe àlejò lọ sibẹ!Ṣé òjò ní baba; àbí, baba wo ló sì bí ìrì?Nítorí àwọn Sadusi sọ pé kò sí ajinde, bẹ́ẹ̀ ni kò sí angẹli tabi àwọn ẹ̀mí; ṣugbọn àwọn Farisi gbà pé mẹtẹẹta wà. Ta ló lè rí iyawo tí ó ní ìwà rere fẹ́?Ó ṣọ̀wọ́n ju ohun ọ̀ṣọ́ olówó iyebíye lọ.16. Ẹyin oníwéé! Dájúdájú: òjíṣẹ
“Nitori naa, so fun un pe, emi OLUWA awon omo ogun ni ‘mo mu un wa lati inu papa, nibi ti o ti n da eran, pe ki o wa joba lori, awon eniyan mi, Israeli. Nitori pe awon eniyan wonyi ti ko mi sile, won ti so ibi di alaimo pelu turari ti won n sun si awon orisa ti awon, ati awon baba won, ati awon oba Juda ko mo ri. Won ti pa awon alaise si gbogbo ibi yii. Se ilu olokiki yin naa niyi,ti a ti tedo lati igba atijo!Ti o fi ese re rin lo si ile okeere,ti o se alejo lo sibe!Se ojo ni baba; abi, baba wo lo si bi iri?Nitori awon Sadusi so pe ko si ajinde, bee ni ko si angeli tabi awon emi; sugbon awon Farisi gba pe meteeta wa. Ta lo le ri iyawo ti o ni iwa rere fe?O sowon ju ohun oso olowo iyebiye lo.16. Eyin oniwee! Dajudaju: ojise
Wa ti wá bá yín, o n ṣe àlàyé fún
Wa ti wa ba yin, o n se alaye fun
yín nípa ẹ̀Ọpọòlọpọ ohun tí ẹ̀yin ti fi
yin nipa eOpoolopo ohun ti eyin ti fi
pamọ nínú ìwé náà, 0 sì tún n ṣe
pamo ninu iwe naa, 0 si tun n se
àmúòjúkúrò ẹ̀pòlọpò. Dájúdájú ìmọ
amuojukuro epolopo. Dajudaju imo
lẹ̀ kan ti tò yín wá láti òdò Allah àti
le kan ti to yin wa lati odo Allah ati
ìwé kan tí ô yanjú.
iwe kan ti o yanju.
17. Nipa rẹ̀ ni Allah máa n tọ ẹni tò
17. Nipa re ni Allah maa n to eni to
bá tẹ̀lé ìyénú Rẹ̀ sí ònà àlááfíà, Ò sì
ba tele iyenu Re si ona alaafia, O si
n mú wọn jade kúrò nínú òkùnkùn
n mu won jade kuro ninu okunkun
bọ sí inú ìmélẹ̀ pẹ̀lú ìyònda Rẹ̀, Ò sì
bo si inu imele pelu iyonda Re, O si
fì tọ wọn sí ọnà tí 0 tQ.
fi to won si ona ti 0 tQ.
18. Dájúdájú àwọn tò n wí pé,
18. Dajudaju awon to n wi pe,
'Dájúdájú. Allah ni Masihu, ọmọ
'Dajudaju. Allah ni Masihu, omo
Mariam, ti ṣe àìgbàgbọ'. Sọ pé; 'Ta
Mariam, ti se aigbagbo'. So pe; 'Ta
lô ní agbára kan ju Allah lọ, tí Òun
lo ni agbara kan ju Allah lo, ti Oun
bá fẹ pa Masihu, ọmọ Mariam rẹ àti
ba fe pa Masihu, omo Mariam re ati
ìyá rẹ̀ àti gbogbo ohun tí n bẹ ní ori
iya re ati gbogbo ohun ti n be ni ori
ilẹ̀ pátápátá?" Nígbà tí ô jẹ̀ pé ti
ile patapata?" Nigba ti o je pe ti
Allah ni ìjọba. àwọn ọrun. àti ayé àti
Allah ni ijoba. awon orun. ati aye ati
ṣẹ̀dá ohun tí ô bá wù Ú. Allah sì jẹ
seda ohun ti o ba wu U. Allah si je
Alagbara lôòrí ohun gbogbo.
Alagbara loori ohun gbogbo.
19. Àwọn Yàhúdí àti. àwọn
19. Awon Yahudi ati. awon
Nasara sọ pé: - Àwa ni ọmọ Allah
Nasara so pe: - Awa ni omo Allah
àti àyànfẹ Rẹ̀"; sọ fún wọn pé:
ati ayanfe Re"; so fun won pe:
Béṣe nígbà náà tí Ò fi fì jẹ yín níyà àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yin? Kàkà bẹ̀ẹ̀ ẹ̀dá abara ni yín nínú àwọn ẹ̀dá tí Ô dá. Òun a máa fi orí jin ẹni tí O
Bese nigba naa ti O fi fi je yin niya awon ese yin? Kaka bee eda abara ni yin ninu awon eda ti O da. Oun a maa fi ori jin eni ti O
bá wù Ú, A sì máa jẹ ẹni tí O bá
ba wu U, A si maa je eni ti O ba
wù Ú níyà. Tí Allah sì ni ìjọba
wu U niya. Ti Allah si ni ijoba
àwọn ọrun àti ayé àti ohun
awon orun ati aye ati ohun
Rẹ̀ sì ni ìpadàsí.
Re si ni ipadasi.
“Ní ọjọ́ kẹẹdogun oṣù keje yìí, ẹ óo máa ní àpèjọ mímọ́, ẹ kò ní ṣe iṣẹ́ kankan fún ọjọ́ meje tí ẹ óo fi ṣe àjọ̀dún náà. Àjọ̀dún àyẹ́sí ni fún OLUWA. Bẹ́ẹ̀ ni eniyan ṣe tẹ ara rẹ̀ lórí batí ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀.Oluwa, máṣe dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n.Èmi OLUWA yóo pàṣẹ pé kí ibukun mi wà lórí yín ní ọdún kẹfa tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé ilẹ̀ yóo so èso tí yóo to yín jẹ fún ọdún mẹta. Wọ́n mọ̀ pé nígbà tí wọ́n pa Stefanu, ẹlẹ́rìí rẹ, bí mo ti dúró nìyí, tí mò ń kan sáárá sí àwọn tí ó pa á tí mò ń ṣọ́ aṣọ wọn.’ Bí ọmọdé bá mọ ayò, ẹyọ la ó fi pa á.
“Ni ojo keedogun osu keje yii, e oo maa ni apejo mimo, e ko ni se ise kankan fun ojo meje ti e oo fi se ajodun naa. Ajodun ayesi ni fun OLUWA. Bee ni eniyan se te ara re lori bati o si re ara re sile.Oluwa, mase dari ese won ji won.Emi OLUWA yoo pase pe ki ibukun mi wa lori yin ni odun kefa tobee ti o fi je pe ile yoo so eso ti yoo to yin je fun odun meta. Won mo pe nigba ti won pa Stefanu, elerii re, bi mo ti duro niyi, ti mo n kan saara si awon ti o pa a ti mo n so aso won.’ Bi omode ba mo ayo, eyo la o fi pa a.
Paulu dé Dabe ati Listira. Onigbagbọ kan tí ń jẹ́ Timoti wà níbẹ̀. Ìyá rẹ̀ jẹ́ Juu tí ó gba Jesu gbọ́; ṣugbọn Giriki ni baba rẹ̀. Ó bá lọ sí iwájú díẹ̀, ó dojúbolẹ̀, ó ń gbadura pé bí ó bá ṣeéṣe kí àkókò yìí kọjá lórí òun. Ní àkókò náà,OLUWA yóo fìyà jẹ àwọn ogun ọ̀run, lọ́run;ati àwọn ọba ayé, lórí ilẹ̀ ayé.Igun mẹrẹẹrin ìlú náà dọ́gba, bákan náà ni gígùn rẹ̀ ati ìbú rẹ̀. Ó fi ọ̀pá ìwọnlẹ̀ náà wọn ìlú náà. Bákan náà ni gígùn rẹ̀, ati ìbú rẹ̀, ati gíga rẹ̀. Ó jẹ́ ẹẹdẹgbẹjọ (1500) ibùsọ̀. Kò lè ṣe iṣẹ́ ìyanu pupọ níbẹ̀ nítorí wọn kò ní igbagbọ.Nígbà tí ó ṣe, Esau kó àwọn aya rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin, gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, àwọn mààlúù rẹ̀, àwọn ẹran ọ̀sìn rẹ̀, ati gbogbo ohun ìní rẹ̀ tí ó ti kójọ ní ilẹ̀ Kenaani, ó kó kúrò ní ilẹ̀ Kenaani lọ́dọ̀ Jakọbu, arakunrin rẹ̀. “Nígbà tí ẹ̀mí èṣù bá jáde kúrò ninu ẹnìkan, á máa wá ilẹ̀ gbígbẹ kiri láti sinmi. Nígbà tí kò bá rí, á ní, ‘N óo tún pada sí ilé mi níbi tí mo ti jáde kúrò.’ “Kí ó tó bẹ̀rẹ̀ sí rọbí, ó ti bímọ. Kí ìrora obí tó mú un,ó ti bí ọmọkunrin kan.Ó bọ oriṣa Baali, ó sì mú OLUWA Ọlọrun Israẹli bínú ní gbogbo ọ̀nà bí baba rẹ̀ ti ṣe.Saulu bá wí fún gbogbo Israẹli pé, “Gbogbo yín, ẹ dúró ní apá kan, èmi ati Jonatani, ọmọ mi, yóo dúró ní apá keji.”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ṣe ohun tí ó bá tọ́ lójú rẹ.”Ẹ kò gbọdọ̀ fi ìyá ẹran ati ọmọ rẹ̀ rúbọ ní ọjọ́ kan náà; kì báà jẹ́ mààlúù, tabi aguntan, tabi ewúrẹ́. Wọ́n lọ títí dé àfonífojì Eṣikolu, wọ́n wo ilẹ̀ náà. Ṣugbọn nígbà tí wọ́n pada dé, wọ́n mú kí ọkàn àwọn ọmọ Israẹli rẹ̀wẹ̀sì, kí wọn má lè lọ sí ilẹ̀ tí OLUWA ti fi fún wọn. nígbà tí ojú yín n ṣe bàìbàì tí àyà
Paulu de Dabe ati Listira. Onigbagbo kan ti n je Timoti wa nibe. Iya re je Juu ti o gba Jesu gbo; sugbon Giriki ni baba re. O ba lo si iwaju die, o dojubole, o n gbadura pe bi o ba seese ki akoko yii koja lori oun. Ni akoko naa,OLUWA yoo fiya je awon ogun orun, lorun;ati awon oba aye, lori ile aye.Igun mereerin ilu naa dogba, bakan naa ni gigun re ati ibu re. O fi opa iwonle naa won ilu naa. Bakan naa ni gigun re, ati ibu re, ati giga re. O je eedegbejo (1500) ibuso. Ko le se ise iyanu pupo nibe nitori won ko ni igbagbo.Nigba ti o se, Esau ko awon aya re, awon omo re lokunrin ati lobinrin, gbogbo awon ara ile re, awon maaluu re, awon eran osin re, ati gbogbo ohun ini re ti o ti kojo ni ile Kenaani, o ko kuro ni ile Kenaani lodo Jakobu, arakunrin re. “Nigba ti emi esu ba jade kuro ninu enikan, a maa wa ile gbigbe kiri lati sinmi. Nigba ti ko ba ri, a ni, ‘N oo tun pada si ile mi nibi ti mo ti jade kuro.’ “Ki o to bere si robi, o ti bimo. Ki irora obi to mu un,o ti bi omokunrin kan.O bo orisa Baali, o si mu OLUWA Olorun Israeli binu ni gbogbo ona bi baba re ti se.Saulu ba wi fun gbogbo Israeli pe, “Gbogbo yin, e duro ni apa kan, emi ati Jonatani, omo mi, yoo duro ni apa keji.”Won da a lohun pe, “Se ohun ti o ba to loju re.”E ko gbodo fi iya eran ati omo re rubo ni ojo kan naa; ki baa je maaluu, tabi aguntan, tabi ewure. Won lo titi de afonifoji Esikolu, won wo ile naa. Sugbon nigba ti won pada de, won mu ki okan awon omo Israeli rewesi, ki won ma le lo si ile ti OLUWA ti fi fun won. nigba ti oju yin n se baibai ti aya
yin sì n já, tí ẹ sì n ro ẹ̀ròkerò
yin si n ja, ti e si n ro erokero
12. Níbẹ̀, a dán àwọn onígbàgbọ
12. Nibe, a dan awon onigbagbo
òdodo wò, a sì mì wọn ní mímì tí
ododo wo, a si mi won ni mimi ti
ô le koko.
o le koko.
13. Nígbà ti àwọn alágàbàgebò
13. Nigba ti awon alagabagebo
àti àwọn tí àrùn n bẹ lọkàn wọn
ati awon ti arun n be lokan won
ìlérí kankan fún wa ju ìtànjẹ lọ.
ileri kankan fun wa ju itanje lo.
14. Nígbà tí apá kan nínú wọn wi
14. Nigba ti apa kan ninu won wi
pé, 'Ẹyin. ará ìlú, Yathrib
pe, 'Eyin. ara ilu, Yathrib
(Madina). kò sí ibùdú fún yín,
(Madina). ko si ibudu fun yin,
nitorí náà, ẹ padà." Báyìí ni apá
nitori naa, e pada." Bayii ni apa
kan nínú wọn ṣe tọrọ ààyẹ̀. lọdọ
kan ninu won se toro aaye. lodo
Anabi, wọn wi pé, 'daájúdájú ilé
Anabi, won wi pe, 'daajudaju ile
wa wà láìláàbò, bẹ̀ẹ̀ sì ni ilé wọn
wa wa lailaabo, bee si ni ile won
kò si ní òfifo, wọn kàn n wá ẹ̀nà
ko si ni ofifo, won kan n wa ena
lati sálọ ni.
lati salo ni.
15. Bí (àwọn ọta) bá wọlú wá bá
15. Bi (awon ota) ba wolu wa ba
wọn láti àwọn àyíká (ìlú náà) tí
won lati awon ayika (ilu naa) ti
àwọn kan sì sọ fún wọn pe ki
awon kan si so fun won pe ki
wọn -. lọwọ nínú rògbòdìyàn náà
won -. lowo ninu rogbodiyan naa
wọn ìbá ṣe bẹ̀ẹ̀ lọgàán, wọn kì bá
won iba se bee logaan, won ki ba
sì ti rosẹ̀ bí kò ṣe fún ìgbà diẹ̀.
si ti rose bi ko se fun igba die.
16. Àti pé wọn ti bá Allah ṣe
16. Ati pe won ti ba Allah se
àdéhùn tẹlẹ̀tẹlẹ̀ láti má ṣẹ̀rípadà.
adehun teletele lati ma seripada.
Àdéhùn Allah sì j$ ohun tí a o
Adehun Allah si j$ ohun ti a o
bòẹ̀rẹ̀ lJỌwọ wọn.
boere lJOwo won.
17. Sọ pé, 'sisálọ kì yòò ṣe yín
17. So pe, 'sisalo ki yoo se yin
lanfàní, bí ô tilẹ̀ jẹ pé ẹ sá fún ikú
lanfani, bi o tile je pe e sa fun iku
tàbí pípani, nígbà náà ẹ̀yin yúòò
tabi pipani, nigba naa eyin yuoo
Níwájú ẹnu ọ̀nà ìhà àríwá, ni ẹnu ọ̀nà gbọ̀ngàn inú wà bí ó ti wà níwájú ẹnu ọ̀nà ti ìlà oòrùn. Ọkunrin náà wọn ibẹ̀ láti ẹnu ọ̀nà kan sí ikeji, ó jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).Ṣé ẹ rò pé mò ń parọ́ ni?Àbí n kò mọ nǹkan burúkú yàtọ̀?nígbà tí ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ń tàn sí mi lórí,tí mo kọjá ninu òkùnkùn pẹlu ìmọ́lẹ̀ rẹ̀;Dira ogun, kí o sì wà ní ìmúrasílẹ̀, ìwọ ati gbogbo eniyan tí wọ́n pé yí ọ ká, kí o jẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́ fún wọn. Ṣugbọn wọn óo dáhùn fún ìwà wọn níwájú ẹni tí ó ṣetán láti ṣe ìdájọ́ alààyè ati òkú. Palali, ọmọ Usai ṣe àtúnṣe ibi tí ó kọjú sí Igun Odi ati ilé ìṣọ́, láti òkè ilé ọba níbi ọgbà àwọn olùṣọ́. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Pedaaya, ọmọ Paroṣi, Lẹ́yìn náà, ó bí ọmọkunrin mìíràn, ó sọ ọ́ ní Abeli. Iṣẹ́ darandaran ni Abeli ń ṣe, Kaini sì jẹ́ àgbẹ̀. Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, àwọn eniyan náà dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, wọ́n tẹ́ pẹpẹ kan, wọ́n sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia níbẹ̀. 9, Dájúdájú àwọn (tô. gbàgbọ
Niwaju enu ona iha ariwa, ni enu ona gbongan inu wa bi o ti wa niwaju enu ona ti ila oorun. Okunrin naa won ibe lati enu ona kan si ikeji, o je ogorun-un (100) igbonwo (mita 45).Se e ro pe mo n paro ni?Abi n ko mo nnkan buruku yato?nigba ti imole re n tan si mi lori,ti mo koja ninu okunkun pelu imole re;Dira ogun, ki o si wa ni imurasile, iwo ati gbogbo eniyan ti won pe yi o ka, ki o je olori eso fun won. Sugbon won oo dahun fun iwa won niwaju eni ti o setan lati se idajo alaaye ati oku. Palali, omo Usai se atunse ibi ti o koju si Igun Odi ati ile iso, lati oke ile oba nibi ogba awon oluso. Leyin re ni Pedaaya, omo Parosi, Leyin naa, o bi omokunrin miiran, o so o ni Abeli. Ise darandaran ni Abeli n se, Kaini si je agbe. Nigba ti o di ojo keji, awon eniyan naa dide ni owuro kutukutu, won te pepe kan, won si ru ebo sisun ati ebo alaafia nibe. 9, Dajudaju awon (to. gbagbo
lododo, tí wọn sì n ṣe IṢẹ rere,
lododo, ti won si n se ISe rere,
tiwọn ni àwọn ọgbà ìdẹ̀ra.
tiwon ni awon ogba idera.
10. Wọn yòò máa gbé ibẹ̀, òdodo
10. Won yoo maa gbe ibe, ododo
ni àdéhùn Allah... Òun sì ni
ni adehun Allah... Oun si ni
Alagbára, Ọlọgbọn jùlọ.
Alagbara, Ologbon julo.
11. Ô dá òrun láìsí òpò kankan tí
11. O da orun laisi opo kankan ti
ẹ lẹ̀ fọjú rí, Ô sì fi àwọn òkẹ̀
e le foju ri, O si fi awon oke
nlanlaá rinlẹ̀ ṣinṣin sôrí ilẹ̀ kí O lẹ̀
nlanlaa rinle sinsin sori ile ki O le
máa mú yín rò; O sì tan onírúurú
maa mu yin ro; O si tan oniruuru
àwọn ẹ̀dá ká sôrí ilẹ̀. Àti pé A f
awon eda ka sori ile. Ati pe A f
sọ omi kalẹ̀ láti run wá, A sì fi n
so omi kale lati run wa, A si fi n
mú onímurú àwọn ẹ̀so abiyì jáde
mu onimuru awon eso abiyi jade
lati inú rẹ̀.
lati inu re.
12. Éyí ni ìsẹ̀dá Allah, nítorí náà,
12. Eyi ni iseda Allah, nitori naa,
ẹ fi ohun tí àwọn mìíràn tí 0 yàtò
e fi ohun ti awon miiran ti 0 yato
sí I da hàn Mí.. Ṣùgbọn àwọn
si I da han Mi.. Sugbon awon
alábòsí n bẹ nínú ìṣìnà ti 0 hàn
alabosi n be ninu isina ti 0 han
13. Dájúdájú A. fún Lukmaan
13. Dajudaju A. fun Lukmaan
lọgbọn ìjìnlẹ̀ pé "Máa dúpẹ fún
logbon ijinle pe "Maa dupe fun
Allah:?, ẹnikẹni tú bá n dúpẹ, ô n
Allah:?, enikeni tu ba n dupe, o n
dúpẹ fún ẹ̀mí ara rẹ̀, ẹni to bá sìn
dupe fun emi ara re, eni to ba sin
ṣe àìmoore, dájúdájú Allah TO tán,
se aimoore, dajudaju Allah TO tan,
Ẹni ti gbogbo ìyìn tọ sí ni.
Eni ti gbogbo iyin to si ni.
14. Nígbà tí Lukmaan sọ fún ọmọ
14. Nigba ti Lukmaan so fun omo
rẹ̀ nígbà tí o ṣí i létí pé "Ìwọ ọmọ
re nigba ti o si i leti pe "Iwo omo
mi, má ṣe bá Allah wá orogún.
mi, ma se ba Allah wa orogun.
Dájúdájú, ìbá Allah wá orogún jẹ
Dajudaju, iba Allah wa orogun je
àbòsí tí ô tobi.
abosi ti o tobi.
15. A sì ti pa ẹ̀nìyàn láṣẹ nípa
15. A si ti pa eniyan lase nipa