diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
rù tì nínú oyún láti orí ìnira kan sí
ru ti ninu oyun lati ori inira kan si
OLUWA yóo mú ìfẹ́ rẹ̀ ṣẹ lórí mi,OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.Má kọ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ sílẹ̀.“Bí mo bá gbójú lé wúrà,tí mo sì fi ojúlówó wúrà ṣe igbẹkẹle mi,Àwọn oníṣòwò tí ń lo ràkúnmíyà kúrò ní ọ̀nà wọn, wọ́n ń wá omi kiriwọ́n kiri títí wọ́n fi ṣègbé ninu aṣálẹ̀.Bákan náà, àwọn ará Memfisi ati Tapanhesi ti fọ́ adé orí rẹ̀.Ẹ óo lé àwọn ọ̀tá yín jáde, ẹ óo sì máa fi idà pa wọ́n. Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ burẹdi tí ó ní ìwúkàrà ninu pẹlu ẹbọ náà; ọjọ́ meje ni ẹ óo fi jẹ ẹ́ pẹlu burẹdi tí kò ní ìwúkàrà. Oúnjẹ náà jẹ́ oúnjẹ ìpọ́njú, nítorí pé ìkánjú ni ẹ fi jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti; ẹ óo sì lè máa ranti ọjọ́ náà tí ẹ kúrò ní ilẹ̀ Ijipti ní gbogbo ọjọ́ ayé yín. The wicked person does a little wickedness to himself or herself.
OLUWA yoo mu ife re se lori mi,OLUWA, ife re ti ki i ye wa titi lae.Ma ko ise owo re sile.“Bi mo ba gboju le wura,ti mo si fi ojulowo wura se igbekele mi,Awon onisowo ti n lo rakunmiya kuro ni ona won, won n wa omi kiriwon kiri titi won fi segbe ninu asale.Bakan naa, awon ara Memfisi ati Tapanhesi ti fo ade ori re.E oo le awon ota yin jade, e oo si maa fi ida pa won. E ko gbodo je buredi ti o ni iwukara ninu pelu ebo naa; ojo meje ni e oo fi je e pelu buredi ti ko ni iwukara. Ounje naa je ounje iponju, nitori pe ikanju ni e fi jade kuro ni ile Ijipti; e oo si le maa ranti ojo naa ti e kuro ni ile Ijipti ni gbogbo ojo aye yin. The wicked person does a little wickedness to himself or herself.
Ní ọjọ́ náà, wọ́n yan àwọn kan láti mójútó àwọn ilé ìṣúra, ati ọrẹ tí àwọn eniyan dájọ, àwọn èso àkọ́so, ati ìdámẹ́wàá, àwọn tí wọ́n yàn ni wọ́n ń mójútó pípín ẹ̀tọ́ àwọn alufaa ati ti àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìlú wọn, bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ ninu ìwé òfin. Inú àwọn ará ilẹ̀ Juda dùn pupọ sí àwọn alufaa ati sí àwọn ọmọ Lefi tí wọn ń ṣe iṣẹ́ ìsìn. Kí olukuluku wí fún ọmọ rẹ̀ ní ọjọ́ náà pé, ‘Nítorí ohun tí OLUWA ṣe fún mi, nígbà tí ó mú mi jáde láti ilẹ̀ Ijipti wá, ni mo fi ń ṣe ohun tí mò ń ṣe yìí.’ Ẹ yin OLUWA!Ẹ yin OLUWA, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run,ẹ yìn ín lókè ọ̀run.Oríṣìíríṣìí iṣẹ́ ni ó wà, ṣugbọn Ọlọrun kan náà ní ń ṣe ohun gbogbo ninu gbogbo eniyan. Ǹjẹ́, ìwọ mú gbogbo nǹkan wọnyi kúrò wò, o óo rí i pé yóo sọ̀rọ̀ àfojúdi sí ọ lójú ara rẹ.” Bí a bá lé ẹni, tí a kò bá ẹni, ìwọ̀n là ḿbá ẹni-í ṣọ̀tá mọ.
Ni ojo naa, won yan awon kan lati mojuto awon ile isura, ati ore ti awon eniyan dajo, awon eso akoso, ati idamewaa, awon ti won yan ni won n mojuto pipin eto awon alufaa ati ti awon omo Lefi, gege bi ilu won, bi o ti wa ni akosile ninu iwe ofin. Inu awon ara ile Juda dun pupo si awon alufaa ati si awon omo Lefi ti won n se ise isin. Ki olukuluku wi fun omo re ni ojo naa pe, ‘Nitori ohun ti OLUWA se fun mi, nigba ti o mu mi jade lati ile Ijipti wa, ni mo fi n se ohun ti mo n se yii.’ E yin OLUWA!E yin OLUWA, eyin eda orun,e yin in loke orun.Orisiirisii ise ni o wa, sugbon Olorun kan naa ni n se ohun gbogbo ninu gbogbo eniyan. Nje, iwo mu gbogbo nnkan wonyi kuro wo, o oo ri i pe yoo soro afojudi si o loju ara re.” Bi a ba le eni, ti a ko ba eni, iwon la mba eni-i sota mo.
Bí ikún bá jẹ, bí ikún bá mu, ikún a wo oòrùn alẹ́.
Bi ikun ba je, bi ikun ba mu, ikun a wo oorun ale.
Peteru sọ fún un pé, “Wò ó ná! Àwa ti fi ohun gbogbo tí a ní sílẹ̀, a sì ti ń tẹ̀lé ọ.”“Mo ha gbọdọ̀ yọwọ́ lọ́rọ̀ yín ẹ̀yin Efuraimu?Mo ha gbọdọ̀ kọ̀ ọ́ sílẹ̀, Israẹli?Mo ha gbọdọ̀ pa ọ́ run bí mo ti pa Adimai run;kí n ṣe sí ọ bí mo ti ṣe sí Seboimu?Ọkàn mi kò gbà á,àánú yín a máa ṣe mí. pé kí o mú gbogbo àṣẹ tí o ti gbà ṣẹ láìsí àléébù ati láìsí ẹ̀gàn títí Oluwa wa Jesu Kristi yóo fi farahàn. “Aṣọ títa mẹ́wàá ni kí o fi ṣe inú àgọ́ mi, kí aṣọ náà jẹ́ aṣọ ọ̀gbọ̀ funfun, kí wọ́n dárà sí aṣọ náà pẹlu àwọ̀ aró, ati àwọ̀ elése àlùkò ati àwọ̀ pupa, kí àwọn tí wọ́n bá mọ iṣẹ́ ọnà ya àwòrán Kerubu sí ara gbogbo aṣọ títa náà. “Ṣugbọn nígbà tí ẹ bá rí ẹ̀gbin burúkú náà tí ó dúró níbi tí kò yẹ– (kí ó yé ẹni tí ń ka ìwé yìí)– nígbà náà, kí àwọn tí ó wà ní ilẹ̀ Judia sálọ sí orí òkè. If the arms cannot encompass the silk-cotton tree, they may encompass its root.
Peteru so fun un pe, “Wo o na! Awa ti fi ohun gbogbo ti a ni sile, a si ti n tele o.”“Mo ha gbodo yowo loro yin eyin Efuraimu?Mo ha gbodo ko o sile, Israeli?Mo ha gbodo pa o run bi mo ti pa Adimai run;ki n se si o bi mo ti se si Seboimu?Okan mi ko gba a,aanu yin a maa se mi. pe ki o mu gbogbo ase ti o ti gba se laisi aleebu ati laisi egan titi Oluwa wa Jesu Kristi yoo fi farahan. “Aso tita mewaa ni ki o fi se inu ago mi, ki aso naa je aso ogbo funfun, ki won dara si aso naa pelu awo aro, ati awo elese aluko ati awo pupa, ki awon ti won ba mo ise ona ya aworan Kerubu si ara gbogbo aso tita naa. “Sugbon nigba ti e ba ri egbin buruku naa ti o duro nibi ti ko ye– (ki o ye eni ti n ka iwe yii)– nigba naa, ki awon ti o wa ni ile Judia salo si ori oke. If the arms cannot encompass the silk-cotton tree, they may encompass its root.
Bí n kò bá wá láti bá wọn sọ̀rọ̀, wọn kì bá tí ní ẹ̀ṣẹ̀. Ṣugbọn nisinsinyii, wọn kò ní àwáwí fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn. A-fàtẹ́lẹwọ́-fanná kì í dúró.
Bi n ko ba wa lati ba won soro, won ki ba ti ni ese. Sugbon nisinsinyii, won ko ni awawi fun ese won. A-fatelewo-fanna ki i duro.
Mo dákẹ́, n ò sọ nǹkankan;n ò tilẹ̀ dá sí ọ̀rọ̀ rere pàápàá;sibẹ ìpọ́njú mi ń pọ̀ sí iẹni tí ó lè máa ṣáájú wọn lójú ogun, kí àwọn eniyan rẹ má baà wà bí aguntan tí kò ní olùṣọ́.” He-who-carries-live-coals-in-his-palm does not tarry.
Mo dake, n o so nnkankan;n o tile da si oro rere paapaa;sibe iponju mi n po si ieni ti o le maa saaju won loju ogun, ki awon eniyan re ma baa wa bi aguntan ti ko ni oluso.” He-who-carries-live-coals-in-his-palm does not tarry.
Bí a bá róbìnrin à lérí ogun; bí a bá róbìnrin à sọ̀rọ̀ ìjà; bí a dé ojú ogun à ba búbú.
Bi a ba robinrin a leri ogun; bi a ba robinrin a soro ija; bi a de oju ogun a ba bubu.
(Àwọn arakunrin rẹ̀ kò gbà á gbọ́ ni wọ́n ṣe sọ bẹ́ẹ̀.)Bí apá ò ká àràbà, apá lè ká egbò ìdí-i rẹ̀.
(Awon arakunrin re ko gba a gbo ni won se so bee.)Bi apa o ka araba, apa le ka egbo idi-i re.
Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, ẹ̀yin ọkọ̀ ojú omi Taṣiṣi, nítorí àwọn ilé ìṣọ́ yín tí ó lágbára ti wó.When the squirrel has eaten, when the squirrel has drunk, the squirrel looks at the setting sun.
E sokun teduntedun, eyin oko oju omi Tasisi, nitori awon ile iso yin ti o lagbara ti wo.When the squirrel has eaten, when the squirrel has drunk, the squirrel looks at the setting sun.
Nítorí náà bí ẹ kò bá ṣe é gbẹ́kẹ̀lé nípa nǹkan owó ti ayé yìí, ta ni yóo fi dúkìá tòótọ́ sí ìkáwọ́ yín? Ọkàn mi mọ́, ṣugbọn n kò wí pé mo pé, Oluwa ni ẹni tí ó ń ṣe ìdájọ́ mi. Wine stays in the home of the miser until it goes sour.
Nitori naa bi e ko ba se e gbekele nipa nnkan owo ti aye yii, ta ni yoo fi dukia tooto si ikawo yin? Okan mi mo, sugbon n ko wi pe mo pe, Oluwa ni eni ti o n se idajo mi. Wine stays in the home of the miser until it goes sour.
A ti yí ayé pada bí amọ̀ tí a fi òǹtẹ̀ tẹ̀,ati bí aṣọ tí a pa láró.OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, “Ẹ ṣara gírí, gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbọ́ ọ̀rọ̀ tí àwọn wolii tí ń sọ láti ìgbà tí a ti fi ìpìlẹ̀ ilé OLUWA àwọn ọmọ ogun lélẹ̀, kí ẹ baà lè kọ́ ilé náà parí. Ó sọ fún Jesu pé, “Ìwọ ni n óo fún ní gbogbo àṣẹ yìí ati ògo rẹ̀, nítorí èmi ni a ti fi wọ́n lé lọ́wọ́, ẹni tí ó bá sì wù mí ni mo lè fún. Ṣugbọn àwọn amòfin kan jókòó níbẹ̀, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí kùn sinu pé, àwọn ìlú Berota, Sibiraimu (tí ó wà ní ààlà Damasku ati Hamati), títí dé Haseri Hatikoni, tí ó wà ní ààlà Haurani. Tìkà toore, ọ̀kan kì í gbé.
A ti yi aye pada bi amo ti a fi onte te,ati bi aso ti a pa laro.OLUWA awon omo ogun ni, “E sara giri, gbogbo eyin ti e n gbo oro ti awon wolii ti n so lati igba ti a ti fi ipile ile OLUWA awon omo ogun lele, ki e baa le ko ile naa pari. O so fun Jesu pe, “Iwo ni n oo fun ni gbogbo ase yii ati ogo re, nitori emi ni a ti fi won le lowo, eni ti o ba si wu mi ni mo le fun. Sugbon awon amofin kan jokoo nibe, won bere si kun sinu pe, awon ilu Berota, Sibiraimu (ti o wa ni aala Damasku ati Hamati), titi de Haseri Hatikoni, ti o wa ni aala Haurani. Tika toore, okan ki i gbe.
Bí a bá tà á, ìbá tó nǹkan bí ọọdunrun (300) owó fadaka, à bá sì fún àwọn talaka.” Báyìí ni wọ́n ń fi ohùn líle bá obinrin náà wí.Ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹ̀dá alààyè mẹrin náà ní apá mẹfa. Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ọpọlọpọ ojú. Wọn kì í sinmi tọ̀sán-tòru, wọ́n ń wí pé,“Mímọ́! Mímọ́! Mímọ́!Oluwa Ọlọrun Olodumare.Ẹni tí ó ti wà, tí ó wà nisinsinyii,tí ó sì ń bọ̀ wá.” Àkàwé ni gbogbo èyí jẹ́ fún àkókò yìí. Àwọn ẹ̀bùn ati ẹbọ tí wọn ń rú nígbà náà kò lè fún àwọn tí ó ń rú wọn ní ìbàlẹ̀ àyà patapata. (N kò fi ẹnu mi ṣẹ̀kí n gbé e ṣépè pé kí ó lè kú);Nítorí Oluwa ń ṣọ́ àwọn olódodo,ó sì dẹ etí sí ẹ̀bẹ̀ wọn.Ṣugbọn ojú Oluwa kan síàwọn tí ó ń ṣe burúkú.” Yóo tún fi ẹ̀rín kún ọ ní ẹ̀rẹ̀kẹ́,ẹnu rẹ yóo kún fún ìhó ayọ̀.Lẹ́yìn rẹ̀ Malikija, ọ̀kan ninu àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà, ṣe àtúnṣe títí dé ilé àwọn iranṣẹ tẹmpili ati ilé àwọn oníṣòwò, níbi tí ó kọjú sí Ẹnu Ọ̀nà Mifikadi, ati títí dé yàrá òkè orígun odi.tí ẹ bá ń búra pẹlu òtítọ́ pé, ‘Bí OLUWA ti wà láàyè,’ lórí ẹ̀tọ́ ati òdodo, àwọn orílẹ̀-èdè yòókù yóo máa fi orúkọ mi súre fún ara wọn, wọn yóo sì máa ṣògo ninu mi.”Bí Satani bá gbé ogun ti ara rẹ̀, báwo ni ìjọba rẹ̀ ṣe lè dúró? Nítorí ẹ̀ ń sọ pé agbára Beelisebulu ni mo fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. “Bí ẹnìkan bá jẹ ohun mímọ́ kan ní ìjẹkújẹ yóo san án pada fún alufaa pẹlu ìdámárùn-ún rẹ̀. Nígbà tí mo lọ sí Jerusalẹmu, àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbààgbà àwọn Juu rojọ́ rẹ̀, wọ́n sì bẹ̀ mí pé kí n dá a lẹ́bi. Ẹ óo wá mi, ẹ óo sì rí mi, bí ẹ bá fi tọkàntọkàn wá mi. Àwọn ìlú tí wọ́n wà ní orí òkè nìwọ̀nyí: Ṣamiri, Ṣugbọn Onani mọ̀ pé ọmọ tí opó náà bá bí kò ní jẹ́ ti òun, nítorí náà, nígbàkúùgbà tí ó bá ń bá opó yìí lòpọ̀, yóo sì da nǹkan ọkunrin rẹ̀ sílẹ̀, kí ó má baà bí ọmọ tí yóo rọ́pò arakunrin rẹ̀. An elder is not present at a market and permit a child's head to rest askew.
Bi a ba ta a, iba to nnkan bi oodunrun (300) owo fadaka, a ba si fun awon talaka.” Bayii ni won n fi ohun lile ba obinrin naa wi.Okookan ninu awon eda alaaye merin naa ni apa mefa. Okookan won ni opolopo oju. Won ki i sinmi tosan-toru, won n wi pe,“Mimo! Mimo! Mimo!Oluwa Olorun Olodumare.Eni ti o ti wa, ti o wa nisinsinyii,ti o si n bo wa.” Akawe ni gbogbo eyi je fun akoko yii. Awon ebun ati ebo ti won n ru nigba naa ko le fun awon ti o n ru won ni ibale aya patapata. (N ko fi enu mi seki n gbe e sepe pe ki o le ku);Nitori Oluwa n so awon olododo,o si de eti si ebe won.Sugbon oju Oluwa kan siawon ti o n se buruku.” Yoo tun fi erin kun o ni ereke,enu re yoo kun fun iho ayo.Leyin re Malikija, okan ninu awon alagbede wura, se atunse titi de ile awon iranse tempili ati ile awon onisowo, nibi ti o koju si Enu Ona Mifikadi, ati titi de yara oke origun odi.ti e ba n bura pelu otito pe, ‘Bi OLUWA ti wa laaye,’ lori eto ati ododo, awon orile-ede yooku yoo maa fi oruko mi sure fun ara won, won yoo si maa sogo ninu mi.”Bi Satani ba gbe ogun ti ara re, bawo ni ijoba re se le duro? Nitori e n so pe agbara Beelisebulu ni mo fi n le awon emi esu jade. “Bi enikan ba je ohun mimo kan ni ijekuje yoo san an pada fun alufaa pelu idamarun-un re. Nigba ti mo lo si Jerusalemu, awon olori alufaa ati awon agbaagba awon Juu rojo re, won si be mi pe ki n da a lebi. E oo wa mi, e oo si ri mi, bi e ba fi tokantokan wa mi. Awon ilu ti won wa ni ori oke niwonyi: Samiri, Sugbon Onani mo pe omo ti opo naa ba bi ko ni je ti oun, nitori naa, nigbakuugba ti o ba n ba opo yii lopo, yoo si da nnkan okunrin re sile, ki o ma baa bi omo ti yoo ropo arakunrin re. An elder is not present at a market and permit a child's head to rest askew.
Lójú ẹni tí ara tù,ìṣòro kì í báni láìnídìí.Lójú rẹ̀, ẹni tí ó bá ṣìṣe ni ìṣòro wà fún.Ohun tí mò ń wí ni pé olukuluku yín ní ń sọ tirẹ̀. Bí ẹnìkan ti ń wí pé. “Ẹ̀yìn Paulu ni èmi wà,” ni ẹlòmíràn ń wí pé. “Ẹ̀yìn Apolo ni èmi wà,” tí ẹlòmíràn tún ń wí pé, “Ẹ̀yìn Peteru ni mo wà ní tèmi.” Ẹlòmíràn sì ń wí pé, “Ẹ̀yìn Kristi ni èmi wà.” Ni mo bá búra pẹlu ibinu,pé wọn kò ní dé ibi ìsinmi mi.”If one has no money to buy a slave, one gives one's chicken a name.
Loju eni ti ara tu,isoro ki i bani lainidii.Loju re, eni ti o ba sise ni isoro wa fun.Ohun ti mo n wi ni pe olukuluku yin ni n so tire. Bi enikan ti n wi pe. “Eyin Paulu ni emi wa,” ni elomiran n wi pe. “Eyin Apolo ni emi wa,” ti elomiran tun n wi pe, “Eyin Peteru ni mo wa ni temi.” Elomiran si n wi pe, “Eyin Kristi ni emi wa.” Ni mo ba bura pelu ibinu,pe won ko ni de ibi isinmi mi.”If one has no money to buy a slave, one gives one's chicken a name.
Àgbà tó bú ọmọdé fi èébú-u rẹ̀ tọrọ.
Agba to bu omode fi eebu-u re toro.
Ṣugbọn ẹ kó ìṣúra jọ fún ara yín ní ọ̀run, níbi tí kòkòrò kò lè bà á jẹ́, bẹ́ẹ̀ ni kò lè dógùn-ún, àwọn olè kò sì lè wá a kàn kí wọ́n jí i lọ níbẹ̀. Ẹnu ya àwọn onigbagbọ tí wọ́n jẹ́ Juu tí wọ́n bá Peteru wá nítorí àwọn tí kì í ṣe Juu rí ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ gbà lọ́fẹ̀ẹ́ ati lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́. Ṣugbọn ẹni àgbéga títí lae ni ọ́, OLUWA.Bí kò bá sí ajinde òkú, a jẹ́ pé a kò jí Kristi dìde. Àwọn kan wá sọ fún Jehoṣafati pé ogun ńlá kan ń bọ̀ wá jà á láti Edomu ní òdìkejì òkun. Wọ́n sọ pé àwọn ọ̀tá náà ti dé Hasasoni Tamari, (tí a tún ń pè ní Engedi). Ṣé ojurere eniyan ni mò ń wá nisinsinyii, tabi ti Ọlọrun? Àbí ohun tí ó wu eniyan ni mo fẹ́ máa ṣe? Bí ó bá jẹ́ pé ohun tí ó wu eniyan ni mò ń ṣe sibẹ, èmi kì í ṣe iranṣẹ Kristi.Ẹ̀yin ará, a fẹ́ kí ẹ mọ ohun tí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun ti ṣe láàrin àwọn ìjọ Masedonia. Àwọn ọmọ ogun tí a kà ninu wọn jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400). Nítorí náà kí ẹ lọ sọ gbogbo orílẹ̀-èdè di ọmọ-ẹ̀yìn mi; kí ẹ máa ṣe ìrìbọmi fún wọn ní orúkọ Baba ati ti Ọmọ ati ti Ẹ̀mí Mímọ́. Bí mo bá ṣe àìdára, mo gbé,ṣugbọn bí mo ṣe dáradára, n kò lè yangàn,nítorí ìbànújẹ́ ati ìtìjú bò mí mọ́lẹ̀.Jesu wí fún un pé, “Mo fẹ́ kí o mọ̀ dájúdájú pé ní alẹ́ yìí, kí àkùkọ tó kọ, ìwọ yóo sẹ́ mi ní ẹẹmẹta.”Jẹ́ kí wọn máa yin OLUWA nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,àní, nítorí àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ó ṣe fún eniyan.Igbe kí-ni-ngó-jẹ-sùn ní ḿpọ̀lẹ.
Sugbon e ko isura jo fun ara yin ni orun, nibi ti kokoro ko le ba a je, bee ni ko le dogun-un, awon ole ko si le wa a kan ki won ji i lo nibe. Enu ya awon onigbagbo ti won je Juu ti won ba Peteru wa nitori awon ti ki i se Juu ri ebun Emi Mimo gba lofee ati lekun-unrere. Sugbon eni agbega titi lae ni o, OLUWA.Bi ko ba si ajinde oku, a je pe a ko ji Kristi dide. Awon kan wa so fun Jehosafati pe ogun nla kan n bo wa ja a lati Edomu ni odikeji okun. Won so pe awon ota naa ti de Hasasoni Tamari, (ti a tun n pe ni Engedi). Se ojurere eniyan ni mo n wa nisinsinyii, tabi ti Olorun? Abi ohun ti o wu eniyan ni mo fe maa se? Bi o ba je pe ohun ti o wu eniyan ni mo n se sibe, emi ki i se iranse Kristi.Eyin ara, a fe ki e mo ohun ti oore-ofe Olorun ti se laarin awon ijo Masedonia. Awon omo ogun ti a ka ninu won je egbaa metadinlogbon o le irinwo (54,400). Nitori naa ki e lo so gbogbo orile-ede di omo-eyin mi; ki e maa se iribomi fun won ni oruko Baba ati ti Omo ati ti Emi Mimo. Bi mo ba se aidara, mo gbe,sugbon bi mo se daradara, n ko le yangan,nitori ibanuje ati itiju bo mi mole.Jesu wi fun un pe, “Mo fe ki o mo dajudaju pe ni ale yii, ki akuko to ko, iwo yoo se mi ni eemeta.”Je ki won maa yin OLUWA nitori ife re ti ki i ye,ani, nitori awon ise iyanu ti o se fun eniyan.Igbe ki-ni-ngo-je-sun ni mpole.
Ṣugbọn ẹ̀yin òkè Israẹli, igi óo hù lórí yín, wọn óo sì so èso fún Israẹli, àwọn eniyan mi, nítorí pé wọn kò ní pẹ́ pada wálé. Kíkìlọ̀ ni ó máa ń kìlọ̀ fún wọn gan-an kí wọn má ṣe fi òun hàn.Jada, arakunrin Ṣamai, bí ọmọ meji: Jeteri ati Jonatani, ṣugbọn Jeteri kò bímọ títí tí ó fi kú. Mo ti rí bí ó ti ń ṣe,ṣugbọn n óo ṣì wò ó sàn;n óo máa darí rẹ̀, n óo tù ú ninu,n óo sì fún àwọn tí ó bá ń ṣọ̀fọ̀ ní Israẹli ní orin ayọ̀.Sanbalati ati Geṣemu ranṣẹ sí mi, wọ́n ní “Wá, jẹ́ kí á pàdé ní ọ̀kan ninu àwọn ìletò tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ono.” Ṣugbọn wọ́n ti pète láti ṣe mí ní ibi. Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà, iná ńlá kan bẹ̀rẹ̀ sí jó. Ṣugbọn OLUWA kò sí ninu iná náà. Lẹ́yìn iná náà, ohùn kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ kan rọra sọ̀rọ̀ jẹ́ẹ́jẹ́.Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọnyi. Nígbà tí Dafidi gbọ́, ó rán Joabu ati gbogbo àwọn akọni jagunjagun rẹ̀ jáde lọ bá wọn. Gbogbo ẹ̀yin tí ẹ̀ ń dáná,tí ẹ tan iná yí ara yín ká,ẹ máa rìn lọ ninu iná tí ẹ dá;ẹ máa la iná tí ẹ fi yí ara yín ká kọjá.Bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe fun yín.Ẹ óo wà ninu ìrora.OLUWA Ọlọrun ní, “Ẹnu ọ̀nà àgbàlá inú tí ó kọjú sí ìlà oòrùn gbọdọ̀ wà ní títì fún ọjọ́ mẹfa tí a fi ń ṣiṣẹ́. Ṣugbọn ẹ máa ṣí i ní ọjọ́ ìsinmi ati ọjọ́ oṣù tuntun. Hamu ni baba Kuṣi, Ijipti, Puti ati Kenaani, Kí o gbé tabili kalẹ̀ ní ọwọ́ òde aṣọ títa náà, kí ọ̀pá fìtílà wà ní apá ìhà gúsù àgọ́ náà, ní òdìkejì tabili náà, kí o sì gbé tabili náà kalẹ̀ ní apá àríwá.Ohun tí ḿbá ahun náwó ẹ̀ ḿbẹ lápò-o ẹ̀.
Sugbon eyin oke Israeli, igi oo hu lori yin, won oo si so eso fun Israeli, awon eniyan mi, nitori pe won ko ni pe pada wale. Kikilo ni o maa n kilo fun won gan-an ki won ma se fi oun han.Jada, arakunrin Samai, bi omo meji: Jeteri ati Jonatani, sugbon Jeteri ko bimo titi ti o fi ku. Mo ti ri bi o ti n se,sugbon n oo si wo o san;n oo maa dari re, n oo tu u ninu,n oo si fun awon ti o ba n sofo ni Israeli ni orin ayo.Sanbalati ati Gesemu ranse si mi, won ni “Wa, je ki a pade ni okan ninu awon ileto ti o wa ni petele Ono.” Sugbon won ti pete lati se mi ni ibi. Leyin isele naa, ina nla kan bere si jo. Sugbon OLUWA ko si ninu ina naa. Leyin ina naa, ohun kelekele kan rora soro jeeje.Eyin ni elerii nnkan wonyi. Nigba ti Dafidi gbo, o ran Joabu ati gbogbo awon akoni jagunjagun re jade lo ba won. Gbogbo eyin ti e n dana,ti e tan ina yi ara yin ka,e maa rin lo ninu ina ti e da;e maa la ina ti e fi yi ara yin ka koja.Bee ni n oo se fun yin.E oo wa ninu irora.OLUWA Olorun ni, “Enu ona agbala inu ti o koju si ila oorun gbodo wa ni titi fun ojo mefa ti a fi n sise. Sugbon e maa si i ni ojo isinmi ati ojo osu tuntun. Hamu ni baba Kusi, Ijipti, Puti ati Kenaani, Ki o gbe tabili kale ni owo ode aso tita naa, ki opa fitila wa ni apa iha gusu ago naa, ni odikeji tabili naa, ki o si gbe tabili naa kale ni apa ariwa.Ohun ti mba ahun nawo e mbe lapo-o e.
Ní tiwa, ó tọ́ bẹ́ẹ̀, nítorí èrè iṣẹ́ wa ni à ń jẹ. Ṣugbọn òun ní tirẹ̀ kò ṣẹ̀ rárá.” Orí 6
Ni tiwa, o to bee, nitori ere ise wa ni a n je. Sugbon oun ni tire ko se rara.” Ori 6
(A sọ ọ kalẹ;
(A so o kale;
1. Ni Orúkọ Allah, Olore ẹ̀fẹ
1. Ni Oruko Allah, Olore efe
Aláàánú jùlọ.
Alaaanu julo.
2. Gbogbo ìyìn jẹ ti Allah, Ẹni tí
2. Gbogbo iyin je ti Allah, Eni ti
Ô dá àwọn òrun àti ayé; ÒÔ sì mú
O da awon orun ati aye; OO si mu
kí (onírúurú) òkùnkùn àti ìmọlẹ̀
ki (oniruuru) okunkun ati imole
wà; síbẹ̀síbẹ̀ àwọn tí kò gbàgbọ n
wa; sibesibe awon ti ko gbagbo n
bá Olúwa wọn wá àfijọ.
ba Oluwa won wa afijo.
3. Òun náà ni Ẹni tí O dá yín láti
3. Oun naa ni Eni ti O da yin lati
inú amẹ̀, Ò sì pinnu àkòkò.
inu ame, O si pinnu akoko.
Àkòkò (mìíràn) sì tún wà tí Ô ti
Akoko (miiran) si tun wa ti O ti
pinnu ní ọdọ ara Rẹ̀. Síbẹ̀síbẹ̀ ẹ
pinnu ni odo ara Re. Sibesibe e
tún n ṣiyẹ̀méjì!
tun n siyemeji!
4. Òun sì ni Allah, (Ọlòrun náà)
4. Oun si ni Allah, (Olorun naa)
ní àwọn ọrun àti ní ayé, Ô mọ
ni awon orun ati ni aye, O mo
ìkòkọ yín àti gbangba yín, Ò sì
ikoko yin ati gbangba yin, O si
mọ ohun tí ẹ n kò jọ.
mo ohun ti e n ko jo.
5. Àmì kan kò sì ní wá bá wọn
5. Ami kan ko si ni wa ba won
nínú àwọn Àmì Olúwa. wọn.
ninu awon Ami Oluwa. won.
àyàfi kí wọn gbúnrí kúrò níbẹ̀.
ayafi ki won gbunri kuro nibe.
6. Nípa bẹ̀ wọn kọ òdodo náà
6. Nipa be won ko ododo naa
nígbà tí ô dé wá bá wọn; ṣùgbọn
nigba ti o de wa ba won; sugbon
láìpẹ ni ìrò ohun tí wọn fi ṣe yẹ̀yẹ
laipe ni iro ohun ti won fi se yeye
máa dé wá bá wọn.
maa de wa ba won.
7. Wọn kò a rí i ni, mélòòmélòò
7. Won ko a ri i ni, meloomeloo
ni àwọn ìran tí A ti parun ṣíwájú
ni awon iran ti A ti parun siwaju
wọn? A fi ààyẹ̀ gbà wọn lori ilẹ̀,
won? A fi aaye gba won lori ile,
ni irú ààyẹ̀ tí a kò fi gba ẹ̀yin, A
ni iru aaye ti a ko fi gba eyin, A
sì Jẹ kí kùrukùru ṣíji DÒò wọn, Ô
si Je ki kurukuru siji DOo won, O
Saulu dáhùn pé, “Ọlọ́run yóo bukun ọ, ọmọ mi, o óo máa ṣe àṣeyọrí ninu gbogbo ohun tí o bá ń ṣe.”Dafidi bá bá tirẹ̀ lọ, Saulu sì pada sí ilé rẹ̀.Kí ẹsẹ̀ keji jẹ́ òkúta emeradi, ati òkúta safire, ati òkúta dayamọndi. Ẹ̀mí sọ pàtó pé nígbà tí ó bá yá, àwọn ẹlòmíràn yóo yapa kúrò ninu ẹ̀sìn igbagbọ, wọn yóo tẹ̀lé àwọn ẹ̀mí ẹ̀tàn ati ẹ̀kọ́ tí ó ti ọ̀dọ̀ àwọn ẹ̀mí èṣù wá. Nígbà tí ẹ bá ń kọjá lọ ní oko ọkà ẹlòmíràn, tí wọn kò tíì kórè, ẹ lè fi ọwọ́ ya ìwọ̀nba tí ẹ lè jẹ, ṣugbọn ẹ kò gbọdọ̀ fi dòjé gé ọkà ọlọ́kà.If a single Colubus monkey sees you, be sure that two hundred of them have seen you.
Saulu dahun pe, “Olorun yoo bukun o, omo mi, o oo maa se aseyori ninu gbogbo ohun ti o ba n se.”Dafidi ba ba tire lo, Saulu si pada si ile re.Ki ese keji je okuta emeradi, ati okuta safire, ati okuta dayamondi. Emi so pato pe nigba ti o ba ya, awon elomiran yoo yapa kuro ninu esin igbagbo, won yoo tele awon emi etan ati eko ti o ti odo awon emi esu wa. Nigba ti e ba n koja lo ni oko oka elomiran, ti won ko tii kore, e le fi owo ya iwonba ti e le je, sugbon e ko gbodo fi doje ge oka oloka.If a single Colubus monkey sees you, be sure that two hundred of them have seen you.
Abiyamọ́ purọ́ mọ́mọ-ọ rẹ̀ jẹun.
Abiyamo puro momo-o re jeun.
Nígbà tí wolii Eliṣa wà ninu àìsàn tí ó le, tí ó sì ń kú lọ, Jehoaṣi, ọba Israẹli lọ bẹ̀ ẹ́ wò, nígbà tí ó rí Eliṣa, ó sọkún, ó sì ń kígbe pé, “Baba mi, baba mi! Ìwọ tí o jẹ́ alátìlẹyìn pataki fún Israẹli!” Surieli ọmọ Abihaili ni yóo jẹ́ olórí wọn. Kí wọ́n pàgọ́ tiwọn sí ìhà àríwá Àgọ́ Àjọ. N óo mú wọn jáde kúrò láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù, n óo kó wọn jọ láti gbogbo ilẹ̀ ayé, n óo sì kó wọn wá sí ilẹ̀ tiwọn. N óo máa bọ́ wọn lórí àwọn òkè Israẹli, lẹ́bàá orísun omi ati gbogbo ibi tí àwọn eniyan ń gbé ní Israẹli. We are discussing pumpkins, a woman asks what we are discussing, and we respond that it is men's talk; after we have gathered the pumpkins, who will cook them?
Nigba ti wolii Elisa wa ninu aisan ti o le, ti o si n ku lo, Jehoasi, oba Israeli lo be e wo, nigba ti o ri Elisa, o sokun, o si n kigbe pe, “Baba mi, baba mi! Iwo ti o je alatileyin pataki fun Israeli!” Surieli omo Abihaili ni yoo je olori won. Ki won pago tiwon si iha ariwa Ago Ajo. N oo mu won jade kuro laarin awon orile-ede yooku, n oo ko won jo lati gbogbo ile aye, n oo si ko won wa si ile tiwon. N oo maa bo won lori awon oke Israeli, lebaa orisun omi ati gbogbo ibi ti awon eniyan n gbe ni Israeli. We are discussing pumpkins, a woman asks what we are discussing, and we respond that it is men's talk; after we have gathered the pumpkins, who will cook them?
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé díẹ̀ ni àwọn ọmọ ogun Siria tí wọ́n wá, sibẹsibẹ OLUWA fi ọpọlọpọ ninu àwọn ọmọ ogun Juda lé wọn lọ́wọ́ nítorí pé wọ́n ti kọ OLUWA Ọlọrun baba wọn sílẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ìdájọ́ Joaṣi ọba. Ó ṣe, ní òkè àwọn odò kan ní ilẹ̀ Sudaniibìkan wà tí àwọn ẹyẹ ti ń fò pẹ̀ẹ̀rẹ̀pẹ̀.“Gbọ́ ohun tí OLUWA sọ, ìwọ ọba Juda, tí o jókòó lórí ìtẹ́ Dafidi, ìwọ ati àwọn ìjòyè rẹ ati àwọn eniyan rẹ, tí wọn ń gba àwọn ẹnubodè wọnyi wọlé: À ńsọ̀rọ̀ elégédé, obìnrín ḿbèrè ohun tí à ńsọ, a ní ọ̀rọ̀ ọkùnrin ni; bí a bá kó elégédé jọ, ta ni yó sè é?
Bi o tile je pe die ni awon omo ogun Siria ti won wa, sibesibe OLUWA fi opolopo ninu awon omo ogun Juda le won lowo nitori pe won ti ko OLUWA Olorun baba won sile. Bee ni won se idajo Joasi oba. O se, ni oke awon odo kan ni ile Sudaniibikan wa ti awon eye ti n fo peerepe.“Gbo ohun ti OLUWA so, iwo oba Juda, ti o jokoo lori ite Dafidi, iwo ati awon ijoye re ati awon eniyan re, ti won n gba awon enubode wonyi wole: A nsoro elegede, obinrin mbere ohun ti a nso, a ni oro okunrin ni; bi a ba ko elegede jo, ta ni yo se e?
Ẹ wò ó! N óo kó wọn wá láti ilẹ̀ àríwá,n óo kó wọn jọ láti òpin ayé.Àwọn afọ́jú ati arọ yóo wà láàrin wọn,ati aboyún ati àwọn tí wọn ń rọbí lọ́wọ́.Ogunlọ́gọ̀ eniyan ni àwọn tí yóo pada wá síbí.Geriṣoni ni baba ńlá àwọn ọmọ Libini ati àwọn ọmọ Ṣimei. Ẹ sọ fún àwọn ọmọ yín nípa rẹ̀,kí àwọn náà sọ fún àwọn ọmọ wọn,kí àwọn ọmọ wọn sì sọ fún àwọn ọmọ tiwọn náà.“Ẹ̀mí OLUWA ń gba ẹnu mi sọ̀rọ̀,ọ̀rọ̀ rẹ̀ wà ní ẹnu mi.Ní oṣù keji ọdún keji tí wọ́n dé sí ilé Ọlọrun ní Jerusalẹmu ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà. Serubabeli, ọmọ Ṣealitieli, ati Jeṣua ọmọ Josadaki, ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, pẹlu àwọn arakunrin wọn yòókù, àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi, ati àwọn tí wọ́n ti ìgbèkùn pada sí Jerusalẹmu. Wọ́n yan àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ti tó ọmọ ogún ọdún tabi jù bẹ́ẹ̀ lọ, láti máa bojútó iṣẹ́ ilé OLUWA. The nursing mother lies against her child to secure food.
E wo o! N oo ko won wa lati ile ariwa,n oo ko won jo lati opin aye.Awon afoju ati aro yoo wa laarin won,ati aboyun ati awon ti won n robi lowo.Ogunlogo eniyan ni awon ti yoo pada wa sibi.Gerisoni ni baba nla awon omo Libini ati awon omo Simei. E so fun awon omo yin nipa re,ki awon naa so fun awon omo won,ki awon omo won si so fun awon omo tiwon naa.“Emi OLUWA n gba enu mi soro,oro re wa ni enu mi.Ni osu keji odun keji ti won de si ile Olorun ni Jerusalemu ni won bere ise naa. Serubabeli, omo Sealitieli, ati Jesua omo Josadaki, ni won bere re, pelu awon arakunrin won yooku, awon alufaa, awon omo Lefi, ati awon ti won ti igbekun pada si Jerusalemu. Won yan awon omo Lefi ti won ti to omo ogun odun tabi ju bee lo, lati maa bojuto ise ile OLUWA. The nursing mother lies against her child to secure food.
Láti òkè ni gbogbo ẹ̀bùn rere ati gbogbo ẹ̀bùn pípé ti ń wá, a máa wá láti ọ̀dọ̀ Baba tí ó dá ìmọ́lẹ̀, baba tí kì í yí pada, tí irú òjìji tíí máa wà ninu ìṣípò pada kò sì sí ninu rẹ̀. Ṣe gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun rẹ pa láṣẹ fún ọ pé kí o ṣe, máa tẹ̀lé ọ̀nà rẹ̀, sì pa àwọn òfin ati ìlànà rẹ̀ mọ́, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ́ ọ sinu ìwé òfin Mose, kí gbogbo ohun tí o bá ń ṣe lè máa yọrí sí rere, níbikíbi tí o bá n lọ. Gbogbo àwọn ọlọ́gbọ́n ati aláfọ̀ṣẹ wá siwaju mi, wọ́n gbìyànjú láti ka àkọsílẹ̀ yìí, kí wọ́n sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, ṣugbọn kò sí ẹni tí ó lè ṣe é. “Ohun tí ó tọ́ ni OLUWA ṣe,nítorí mo ti ṣe àìgbọràn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀;ṣugbọn, ẹ gbọ́, ẹ̀yin eniyan,ẹ kíyèsí ìjìyà mi;wọ́n ti kó àwọn ọdọmọbinrin ati ọdọmọkunrin milọ sí ìgbèkùn.Ọmọ náà dá a lóhùn pé, ‘N kò ní lọ.’ Ṣugbọn lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ó ronupiwada, ó bá lọ. Ṣugbọn mo mọ̀ pé Olùdáǹdè mi ń bẹ láàyè,ati pé, níkẹyìn, yóo dìde dúró lórí ilẹ̀ yóo sì jẹ́rìí mi,“O kú iṣẹ́” ò lè bí aráyé nínú.
Lati oke ni gbogbo ebun rere ati gbogbo ebun pipe ti n wa, a maa wa lati odo Baba ti o da imole, baba ti ki i yi pada, ti iru ojiji tii maa wa ninu isipo pada ko si si ninu re. Se gbogbo ohun ti OLUWA Olorun re pa lase fun o pe ki o se, maa tele ona re, si pa awon ofin ati ilana re mo, gege bi a ti ko o sinu iwe ofin Mose, ki gbogbo ohun ti o ba n se le maa yori si rere, nibikibi ti o ba n lo. Gbogbo awon ologbon ati alafose wa siwaju mi, won gbiyanju lati ka akosile yii, ki won si so itumo re fun mi, sugbon ko si eni ti o le se e. “Ohun ti o to ni OLUWA se,nitori mo ti se aigboran si oro re;sugbon, e gbo, eyin eniyan,e kiyesi ijiya mi;won ti ko awon odomobinrin ati odomokunrin milo si igbekun.Omo naa da a lohun pe, ‘N ko ni lo.’ Sugbon leyin igba die, o ronupiwada, o ba lo. Sugbon mo mo pe Oludande mi n be laaye,ati pe, nikeyin, yoo dide duro lori ile yoo si jerii mi,“O ku ise” o le bi araye ninu.
Àwọn obinrin tí wọn bá Jesu wá láti Galili tẹ̀lé Josẹfu yìí, wọ́n ṣe akiyesi ibojì náà, ati bí a ti ṣe tẹ́ òkú Jesu sinu rẹ̀. ati ogoji ìtẹ́lẹ̀ fadaka, meji meji sí àkànpọ̀ igi kọ̀ọ̀kan. 76. Báyìí ni A sì fi ìjọba àwọn
Awon obinrin ti won ba Jesu wa lati Galili tele Josefu yii, won se akiyesi iboji naa, ati bi a ti se te oku Jesu sinu re. ati ogoji itele fadaka, meji meji si akanpo igi kookan. 76. Bayii ni A si fi ijoba awon
ọrun àti ayé han Ibrahim (kí ô lẹ̀
orun ati aye han Ibrahim (ki o le
tọ ọnà tÒô tọ) kí o sì lò jẹ ọkan
to ona tOo to) ki o si lo je okan
nínú àwọn tí 0 mọ àmọdájú.
ninu awon ti 0 mo amodaju.
77. Nígbà tí ilẹ̀ sì ṣú bá a, ô rí
77. Nigba ti ile si su ba a, o ri
ìràwò kan, ô sì wí pé; 'Eyí ni
irawo kan, o si wi pe; 'Eyi ni
Olúwa mi! Ṣùgbọn nígbà tí ô
Oluwa mi! Sugbon nigba ti o
(ìràwò náà) wò, ô wí pé; 'Emi kò
(irawo naa) wo, o wi pe; 'Emi ko
nífẹ̀ẹ si àwọn (olúwa) tí 0 n Wọ."
nifee si awon (oluwa) ti 0 n Wo."
785. Nígbà tí O si tún rí oṣùpá, tí 6
785. Nigba ti O si tun ri osupa, ti 6
yọ pẹ̀lú ìmọlẹ̀ tí ô tàn ká, ô wí pé,
yo pelu imole ti o tan ka, o wi pe,
Eyí ni Olúwa mi nígbà tí ò sì
Eyi ni Oluwa mi nigba ti o si
Wọ, 0 wi pé: 'Tí Olúwa mi kò bá
Wo, 0 wi pe: 'Ti Oluwa mi ko ba
tọ mi sọnà, dájúdájú ẹ̀mi yòò Jẹ
to mi sona, dajudaju emi yoo Je
òkan nínú àwọn ti Ò. ṣìnà.'
okan ninu awon ti O. sina.'
79. Nígbà tí o sì tún rí òòrùn tí ô
79. Nigba ti o si tun ri oorun ti o
yọ, ô wí pé: 'Eyí ni Olúwa mi,
yo, o wi pe: 'Eyi ni Oluwa mi,
ẹ̀yí ni Òô tôbi jùlọ." Ṣùgbọn nígbà
eyi ni Oo tobi julo." Sugbon nigba
tí 6 tún wò, ô wí pé: 'Ẹyin ẹ̀nìyàn
ti 6 tun wo, o wi pe: 'Eyin eniyan
mi, dájúdájú ẹ̀mi kò lọwọ nínú
mi, dajudaju emi ko lowo ninu
àwọn ohun tí ẹ fi n. wá orogún
awon ohun ti e fi n. wa orogun
(pẹ̀lú Ọlérun).
(pelu Olerun).
80. 'Mo ti dojú mi kọ Ẹni tí Ô dá
80. 'Mo ti doju mi ko Eni ti O da
àwọn ọrun àti ayé, ní ìdúrò déédéé,
awon orun ati aye, ni iduro deedee,
ẹ̀mi kò sì jẹ ọkan nínú àwọn tò n wá
emi ko si je okan ninu awon to n wa
oropún (pẹ̀lú.. Ọlọrun).'
oropun (pelu.. Olorun).'
SI. Àwọn ẹ̀niyàn rẹ̀ sì n bá a jiyàn.
SI. Awon eniyan re si n ba a jiyan.
ÒÔ wi pé: 'Ẹyin a fì bá mi jiyàn nípa
OO wi pe: 'Eyin a fi ba mi jiyan nipa
Allah. nígbà tí Ô ti to mi sônà?
Allah. nigba ti O ti to mi sona?
Emi kò bẹ̀rù ohun tí ẹ mú lôrogún
Emi ko beru ohun ti e mu lorogun
pẹ̀lú Rẹ̀, àyàfi bí Olúwa mi bá fẹ̀
pelu Re, ayafi bi Oluwa mi ba fe
kiní kan.. Olúwa mi rọkiriká ohun
kini kan.. Oluwa mi rokirika ohun
gbogbo nínú ìmọ Rẹ̀. Ẹyin kì yòò a
gbogbo ninu imo Re. Eyin ki yoo a
ṣe ìrántí bí?'
se iranti bi?'
Balogun tí ó wà fún oṣù kẹsan-an ni Abieseri ará Anatoti, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini. Iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000). Nítorí èyí gan-an ni mo fi rán an wá sọ́dọ̀ yín, kí ẹ lè mọ bí gbogbo nǹkan ti ń lọ fún wa, kí ó lè fi ọkàn yín balẹ̀. Ó ní ọpọlọpọ ọkọ̀ ojú omi Taṣiṣi tí wọ́n máa ń bá àwọn ọkọ̀ ojú omi Hiramu lọ sí òkè òkun. Ọdún kẹta kẹta ni wọ́n máa ń pada dé, wọn á sì máa kó ọpọlọpọ wúrà, ati fadaka, eyín erin, ìnàkí, ati ẹyẹ ọ̀kín bọ̀.Hadadi, Tema, Jeturi, Nafiṣi ati Kedema. Ẹni tí ó bá fẹ́ràn arakunrin rẹ̀ ń gbé inú ìmọ́lẹ̀, ohun ìkọsẹ̀ kò sí ninu olúwarẹ̀. The goitered person going in front ruins the fortunes of the one coming behind.
Balogun ti o wa fun osu kesan-an ni Abieseri ara Anatoti, lati inu eya Benjamini. Iye awon ti won wa ninu ipin re je oke kan o le egbaaji (24,000). Nitori eyi gan-an ni mo fi ran an wa sodo yin, ki e le mo bi gbogbo nnkan ti n lo fun wa, ki o le fi okan yin bale. O ni opolopo oko oju omi Tasisi ti won maa n ba awon oko oju omi Hiramu lo si oke okun. Odun keta keta ni won maa n pada de, won a si maa ko opolopo wura, ati fadaka, eyin erin, inaki, ati eye okin bo.Hadadi, Tema, Jeturi, Nafisi ati Kedema. Eni ti o ba feran arakunrin re n gbe inu imole, ohun ikose ko si ninu oluware. The goitered person going in front ruins the fortunes of the one coming behind.
Ìbẹ̀rẹ̀ ìjà dàbí kí eniyan ya odò tí wọn sé,dá a dúró kí ó tó di ńlá.“Majẹmu tí Èmi bá wọn dá nìyí: Ẹ̀mí mi tí mo fi le yín lórí, ati ọ̀rọ̀ mi tí mo fi si yín lẹ́nu, kò gbọdọ̀ kúrò lẹ́nu yín, ati lẹ́nu àwọn ọmọ rẹ, ati lẹ́nu arọmọdọmọ yín, láti àkókò yìí lọ ati títí laelae. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”“Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí àwọn ará Amoni kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn. A mọ̀ pé láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun ni a ti wá, ati pé gbogbo ayé patapata wà lábẹ́ Èṣù.Ó gbé èpè wọ̀ bí ẹ̀wù,kí èpè mù ún bí omi,kí ó sì wọ inú egungun rẹ̀ dé mùdùnmúdùn.Ibi gbogbo ní ńrọ àdàbà lọ́rùn.
Ibere ija dabi ki eniyan ya odo ti won se,da a duro ki o to di nla.“Majemu ti Emi ba won da niyi: Emi mi ti mo fi le yin lori, ati oro mi ti mo fi si yin lenu, ko gbodo kuro lenu yin, ati lenu awon omo re, ati lenu aromodomo yin, lati akoko yii lo ati titi laelae. Emi OLUWA ni mo so bee.”“Iwo omo eniyan, koju si awon ara Amoni ki o si so asotele nipa won. A mo pe lati odo Olorun ni a ti wa, ati pe gbogbo aye patapata wa labe Esu.O gbe epe wo bi ewu,ki epe mu un bi omi,ki o si wo inu egungun re de mudunmudun.Ibi gbogbo ni nro adaba lorun.
Ó sọ aṣálẹ̀ di adágún omi,ó sì sọ ilẹ̀ gbígbẹ di orísun omi.Nígbà tí ó di ìrọ̀lẹ́, ó jókòó láti jẹun pẹlu àwọn mejila.Bí àwọn ọmọ Israẹli bá pa òfin mi mọ́, tí wọ́n sì tẹ̀lé gbogbo ìlànà ati ìdájọ́ mi tí mo fún wọn láti ọwọ́ Mose, n kò ní ṣí wọn nídìí mọ́ lórí ilẹ̀ tí mo ti yàn fún àwọn baba wọn.” Jerameeli tún ní aya mìíràn, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Atara, òun ni ìyá Onamu. wọ́n fà á jáde lọ sí ẹ̀yìn ìlú, wọ́n bá ń sọ ọ́ ní òkúta. Àwọn ẹlẹ́rìí fi ẹ̀wù wọn lélẹ̀ níwájú ọdọmọkunrin kan tí à ń pè ní Saulu. Ó ní bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun jàre, Ọlọrun ka òun kún òpùrọ́,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òun kò dẹ́ṣẹ̀, ọgbẹ́ òun kò ṣe é wòsàn.Mo gbàgbọ́ pé n óo rí oore OLUWA gbàní ilẹ̀ alààyè.ó kó ẹẹdẹgbẹrun (900) kẹ̀kẹ́ ogun onírin rẹ̀ jọ, ó sì pe àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ láti Haroṣeti-ha-goimu títí dé odò Kiṣoni.“Bí mààlúù bá kan eniyan pa, kí wọ́n sọ mààlúù náà ní òkúta pa. Ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ jẹ ẹran rẹ̀; ṣugbọn kí ẹnikẹ́ni má ṣe jẹ ẹni tí ó ni mààlúù náà níyà. Ẹ dárin, ẹ lu samba, ẹ ta hapu dídùn ati lire.Amòfin kan wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún un pé, “Olùkọ́ni, mo fẹ́ máa tẹ̀lé ọ níbikíbi tí o bá ń lọ.”Bí alágẹmọ-ọ́ bá fẹ́ kọjá, ìjàm̀pere ò ní-í jà.
O so asale di adagun omi,o si so ile gbigbe di orisun omi.Nigba ti o di irole, o jokoo lati jeun pelu awon mejila.Bi awon omo Israeli ba pa ofin mi mo, ti won si tele gbogbo ilana ati idajo mi ti mo fun won lati owo Mose, n ko ni si won nidii mo lori ile ti mo ti yan fun awon baba won.” Jerameeli tun ni aya miiran, oruko re n je Atara, oun ni iya Onamu. won fa a jade lo si eyin ilu, won ba n so o ni okuta. Awon elerii fi ewu won lele niwaju odomokunrin kan ti a n pe ni Saulu. O ni bi o tile je pe oun jare, Olorun ka oun kun opuro,bi o tile je pe oun ko dese, ogbe oun ko se e wosan.Mo gbagbo pe n oo ri oore OLUWA gbani ile alaaye.o ko eedegberun (900) keke ogun onirin re jo, o si pe awon omo ogun re jo lati Haroseti-ha-goimu titi de odo Kisoni.“Bi maaluu ba kan eniyan pa, ki won so maaluu naa ni okuta pa. Enikeni ko gbodo je eran re; sugbon ki enikeni ma se je eni ti o ni maaluu naa niya. E darin, e lu samba, e ta hapu didun ati lire.Amofin kan wa sodo re, o so fun un pe, “Olukoni, mo fe maa tele o nibikibi ti o ba n lo.”Bi alagemo-o ba fe koja, ijampere o ni-i ja.
Ẹgbẹta ó dín aadọta (550) ni àwọn lọ́gàálọ́gàá tí Solomoni fi ṣe alákòóso àwọn tí ó ń kó ṣiṣẹ́ tipátipá, níbi oríṣìíríṣìí iṣẹ́ ilé kíkọ́ rẹ̀.Ní oṣù keje ni Iṣimaeli, ọmọ Netanaya ọmọ Eliṣama dé, ìdílé ọba ni ó ti wá, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjòyè ọba. Òun pẹlu àwọn ọkunrin mẹ́wàá bá lọ sọ́dọ̀ Gedalaya ọmọ Ahikamu ní Misipa. Bí wọ́n ṣe ń jẹun lọ́wọ́ ní Misipa, A kì í fi orí wé oríi Mokúṣiré; bí Mokú kú láàárọ̀ a jí lálẹ́.
Egbeta o din aadota (550) ni awon logaalogaa ti Solomoni fi se alakooso awon ti o n ko sise tipatipa, nibi orisiirisii ise ile kiko re.Ni osu keje ni Isimaeli, omo Netanaya omo Elisama de, idile oba ni o ti wa, o si je okan lara awon ijoye oba. Oun pelu awon okunrin mewaa ba lo sodo Gedalaya omo Ahikamu ni Misipa. Bi won se n jeun lowo ni Misipa, A ki i fi ori we orii Mokusire; bi Moku ku laaaro a ji lale.
Àgbà kì í wà lọ́jà kórí ọmọ titun wọ́.
Agba ki i wa loja kori omo titun wo.
Nítorí náà, ẹ má ṣe àníyàn nípa nǹkan ti ọ̀la; nítorí ọ̀la ni nǹkan ti ọ̀la wà fún; wahala ti òní nìkan ti tó fún òní láì fi ti ọ̀la kún un.Iṣẹ́ àwọn ọmọ Geriṣoni ninu Àgọ́ Àjọ nìyí, Itamari ọmọ Aaroni alufaa ni yóo jẹ́ alabojuto wọn.”Dafidi sá fún Saulu ní ọjọ́ náà. Ó sì lọ sọ́dọ̀ Akiṣi, ọba Gati. The sap of the violet tree is what the bachelor uses for soap.
Nitori naa, e ma se aniyan nipa nnkan ti ola; nitori ola ni nnkan ti ola wa fun; wahala ti oni nikan ti to fun oni lai fi ti ola kun un.Ise awon omo Gerisoni ninu Ago Ajo niyi, Itamari omo Aaroni alufaa ni yoo je alabojuto won.”Dafidi sa fun Saulu ni ojo naa. O si lo sodo Akisi, oba Gati. The sap of the violet tree is what the bachelor uses for soap.
Ó bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé náà ní ọjọ́ keji oṣù keji ọdún kẹrin ìjọba rẹ̀. 58. Emi kò ṣáà retí ìpẹ̀sṣé kankan
O bere si ko ile naa ni ojo keji osu keji odun kerin ijoba re. 58. Emi ko saa reti ipesse kankan
lati ọdò wọn; bẹ̀ẹ̀ ni N kò retí pé
lati odo won; bee ni N ko reti pe
kí wọn ô fún Mi lòúnjẹ.
ki won o fun Mi lounje.
59.. Dájúdájú, Allah, Òun ni
59.. Dajudaju, Allah, Oun ni
Olùpẹ̀sẹ̀, Ẹni tí gbogbo agbára n
Olupese, Eni ti gbogbo agbara n
bẹ níkapa Rẹ̀.
be nikapa Re.
60. Nítorí náà, dájúdájú ìyá wà
60. Nitori naa, dajudaju iya wa