diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
ríirán Rẹ̀ sí júlọ. Dájúdájú, ìyẹpẹrẹ
riiran Re si julo. Dajudaju, iyepere
lọdò Allah àti ìyà tí 0 le koko yòò
lodo Allah ati iya ti 0 le koko yoo
bọ lu àwọn òdaràn náà nítorí ẹ̀te
bo lu awon odaran naa nitori ete
wọn.
won.
126. Nitori náà ẹnikẹni tí Allah bá
126. Nitori naa enikeni ti Allah ba
fẹ láti tẹ sônà, Òun yòò ṣípayá
fe lati te sona, Oun yoo sipaya
ọkàn. rẹ̀ fún (gbigba) Islam;
okan. re fun (gbigba) Islam;
ṣùgbòn ní ti ẹni tí Òun bá fé kí ô
sugbon ni ti eni ti Oun ba fe ki o
ṣìnà Òun yòò jẹ kí ọkàn rẹ̀ há
sina Oun yoo je ki okan re ha
gadígádí bí ìgbà tí ô n gòkẹ̀ tô
gadigadi bi igba ti o n goke to
nira. Báyìí ni Allah ṣe n fi ìyà
nira. Bayii ni Allah se n fi iya
ẹlẹgbin jẹ àwọn tí kò gbàgbọ.
elegbin je awon ti ko gbagbo.
127. Eyí ni ònà Olúwa rẹ (tí ò lọ sí
127. Eyi ni ona Oluwa re (ti o lo si
òdò Rẹ̀) tààrà. Dájúdájú, A ti ṣe
odo Re) taara. Dajudaju, A ti se
àlàyé àwọn Àmì Wa lẹ̀kùn-únréré
alaye awon Ami Wa lekun-unrere
fún àwọn ẹ̀nìyàn tí wọn n ṣe ìrántí.
fun awon eniyan ti won n se iranti.
128. Ibùgbé àláfíà n bẹ fún wọn
128. Ibugbe alafia n be fun won
lọdò Olúwa wọn; Òun sì ni Ọrẹ
lodo Oluwa won; Oun si ni Ore
wọn nítorí ohun tí wọn n ṣe.
won nitori ohun ti won n se.
129. Ní ọjọ tí Òun yòò kò gbogbo
129. Ni ojo ti Oun yoo ko gbogbo
wọn jọ lápapò, (Òun yòò sì wí pé,)
won jo lapapo, (Oun yoo si wi pe,)
Ẹyin ìjọ Alujannu! Ẹ n fẹ kí ẹpọlọpọ nínú àwọn ẹ̀nìyàn (máa ṣe tiyin)! Àwọn òrẹ wọn. láàrin àwọn ẹ̀nìyàn náà yòò wi pé, 'Olúwa wa! A ti ṣe ànùfàní fún ara wa, ṣùgbọn (ní ìsinsìnyìí) a ti dé òpin àsìkò tí O yán fún wa. Òun yòô wí pé, 'Iná ni gbé, àyàfi ohun tí Allah bá fẹ. Dájúdájú, Olúwa rẹ ni Ọlọgbọn jùlọ, Olùmẹọ ohun gbogbo. Nígbà náà ni Elifasi, ará Temani, dá Jobu lóhùn, ó ní:Nígbà tí Batiṣeba gbọ́ pé wọ́n ti pa ọkọ òun, ó ṣọ̀fọ̀ rẹ̀. Sibẹsibẹ, nítorí ti Dafidi, OLUWA Ọlọrun fún Abijamu ní ọmọkunrin kan tí ó gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀, ní Jerusalẹmu, tí ó sì dáàbò bo Jerusalẹmu. Nisinsinyii, n óo fojú sílẹ̀, etí mi yóo sì ṣí sí adura tí wọ́n bá gbà níbí yìí. Ẹ fetí sí ìbáwí mi,n óo ṣí ọkàn mi payá fun yín,n óo sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ mi ye yín.Jesu tún wí fún wọn pé, “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé. Ẹni tí ó bá ń tẹ̀lé mi kò ní rìn ninu òkùnkùn, ṣugbọn yóo wá sinu ìmọ́lẹ̀ ìyè.” Òní, “Mò ńlọ”; ọ̀la, “Mò ńlọ,” kò jẹ́ kí àlejò gbin awùsá. Bẹ́ẹ̀ tún ni ìlú Sodomu ati Gomora tí ó dá lẹ́bi, tí ó sì dáná sun. Èyí jẹ́ àpẹẹrẹ ohun tí ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ sí àwọn tí kò bẹ̀rù Ọlọrun. 205. Kínla! wọn ha n kánjú fun ìyà Wa ni bí? 206. Kí ni o rò? Tí A bá jẹ kí wQn. gbádùn. (àwọn. ohun mẹ̀rẹmẹ̀re ayé yìí) fún ẹ̀pọlọpọ ọdún; 207. Lẹ̀hìn náà tí ohun ti a ti fi Jáwọn láyà wá dé wá bá wọn. 208. Ohun tí a ti gbà wọn láàyẹ̀ láti gbádùn kì yòò ṣe wọn lOore kankan. 209. Àwa kò pa ilù kan run rí bí kò ṣe kí o ti ní olùkìlọ. 210. Ìrántí (nìyí); Àwa kì í sì í ṣe alábòsí. 211. Kì í sì i ṣe àwọn ẹni ẹ̀ṣù lé mú un sòkalẹ̀. 212. Kò tọ sí wọn, bẹ̀ẹ̀ ni wọn kò ní agbára rẹ̀. 213. Dájúdájú a tí dínà gbígbọ mọ wọn. 214. Nítorí náà má ṣe pe ọlọrun mìíràn lẹhìn Allah, kí ìwọ má baà jẹ òkan nínú àwọn tí a ô jẹ níyà. 2135. Ki o sì kìlọ fún àwọn ìbátan rẹ toô súnmọ ọ, 216. Kí o sì rẹ̀ ìyẹ (àánú) rẹ síjẹ̀ fún àwọn olùgbàgbọ to n tẹ̀lé ọ. 217. Lẹ̀hìn náà bí wọn bá ṣàìgbọràn sí ọ, sọ pé, 'Emi kò. lọwọ rárá nínú ohun tí ẹ̀ n ṣe.
Eyin ijo Alujannu! E n fe ki epolopo ninu awon eniyan (maa se tiyin)! Awon ore won. laarin awon eniyan naa yoo wi pe, 'Oluwa wa! A ti se anufani fun ara wa, sugbon (ni isinsinyii) a ti de opin asiko ti O yan fun wa. Oun yoo wi pe, 'Ina ni gbe, ayafi ohun ti Allah ba fe. Dajudaju, Oluwa re ni Ologbon julo, Olumeo ohun gbogbo. Nigba naa ni Elifasi, ara Temani, da Jobu lohun, o ni:Nigba ti Batiseba gbo pe won ti pa oko oun, o sofo re. Sibesibe, nitori ti Dafidi, OLUWA Olorun fun Abijamu ni omokunrin kan ti o gori oye leyin re, ni Jerusalemu, ti o si daabo bo Jerusalemu. Nisinsinyii, n oo foju sile, eti mi yoo si si si adura ti won ba gba nibi yii. E feti si ibawi mi,n oo si okan mi paya fun yin,n oo si je ki oro mi ye yin.Jesu tun wi fun won pe, “Emi ni imole aye. Eni ti o ba n tele mi ko ni rin ninu okunkun, sugbon yoo wa sinu imole iye.” Oni, “Mo nlo”; ola, “Mo nlo,” ko je ki alejo gbin awusa. Bee tun ni ilu Sodomu ati Gomora ti o da lebi, ti o si dana sun. Eyi je apeere ohun ti n bo wa sele si awon ti ko beru Olorun. 205. Kinla! won ha n kanju fun iya Wa ni bi? 206. Ki ni o ro? Ti A ba je ki wQn. gbadun. (awon. ohun meremere aye yii) fun epolopo odun; 207. Lehin naa ti ohun ti a ti fi Jawon laya wa de wa ba won. 208. Ohun ti a ti gba won laaye lati gbadun ki yoo se won lOore kankan. 209. Awa ko pa ilu kan run ri bi ko se ki o ti ni olukilo. 210. Iranti (niyi); Awa ki i si i se alabosi. 211. Ki i si i se awon eni esu le mu un sokale. 212. Ko to si won, bee ni won ko ni agbara re. 213. Dajudaju a ti dina gbigbo mo won. 214. Nitori naa ma se pe olorun miiran lehin Allah, ki iwo ma baa je okan ninu awon ti a o je niya. 2135. Ki o si kilo fun awon ibatan re too sunmo o, 216. Ki o si re iye (aanu) re sije fun awon olugbagbo to n tele o. 217. Lehin naa bi won ba saigboran si o, so pe, 'Emi ko. lowo rara ninu ohun ti e n se.
218. Kí o sì gbẹ̀kẹ̀lé Alagbára
218. Ki o si gbekele Alagbara
náà, Aláàánú,
naa, Alaaanu,
Joṣua ọmọ Nuni kún fún ọgbọ́n nítorí pé Mose ti gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, nítorí náà àwọn ọmọ Israẹli ń gbọ́ tirẹ̀, wọ́n sì ń ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún Mose.The masquerader enters a house and claims he did not see Ejonto; Ejonto asked, “Is that a rag that entered the house, or what?”
Josua omo Nuni kun fun ogbon nitori pe Mose ti gbe owo re le e, nitori naa awon omo Israeli n gbo tire, won si n se gege bi ase ti OLUWA pa fun Mose.The masquerader enters a house and claims he did not see Ejonto; Ejonto asked, “Is that a rag that entered the house, or what?”
Nígbà tí Jesu mọ̀ bẹ́ẹ̀, ó bá kúrò níbẹ̀. Ọpọlọpọ eniyan sì tẹ̀lé e, ó sì wo gbogbo wọn sàn. Ọbẹ̀ tóo sè tílé fi jóná wàá sọ ọ́.
Nigba ti Jesu mo bee, o ba kuro nibe. Opolopo eniyan si tele e, o si wo gbogbo won san. Obe too se tile fi jona waa so o.
Ó ní òun óo fi ẹ̀mí kan sinu rẹ̀, tí yóo mú kí ó sá pada sí ilẹ̀ rẹ̀ nígbà tí ó bá gbọ́ ìròyìn kan, òun óo sì jẹ́ kí wọ́n pa á nígbà tí ó bá dé ilẹ̀ rẹ̀.”Ẹnu ya gbogbo eniyan. Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọ láàrin ara wọn pé, “Irú ọ̀rọ̀ wo ni èyí? Nítorí pẹlu àṣẹ ati agbára ni ó fi bá àwọn ẹ̀mí èṣù wí, wọ́n sì ń jáde!” Ewúrẹ́ ò wí pé òun ò ṣọmọ àgùntàn; àgùntàn ló wí pé òun ò ṣọmọ ewúrẹ́.
O ni oun oo fi emi kan sinu re, ti yoo mu ki o sa pada si ile re nigba ti o ba gbo iroyin kan, oun oo si je ki won pa a nigba ti o ba de ile re.”Enu ya gbogbo eniyan. Won bere si so laarin ara won pe, “Iru oro wo ni eyi? Nitori pelu ase ati agbara ni o fi ba awon emi esu wi, won si n jade!” Ewure o wi pe oun o somo aguntan; aguntan lo wi pe oun o somo ewure.
“Wò ó, mo ti pe Besaleli ọmọ Uri, ọmọ ọmọ Huri, láti inú ẹ̀yà Juda. A small god is not a thing to hang from the rafters.
“Wo o, mo ti pe Besaleli omo Uri, omo omo Huri, lati inu eya Juda. A small god is not a thing to hang from the rafters.
Àgbàrá kọ́ ni yó gbèé omi lọ.
Agbara ko ni yo gbee omi lo.
nítorí pé àwọn ọ̀mùtí ati àwọn wọ̀bìà yóo di talaka,oorun àsùnjù a sì máa sọ eniyan di alákìísà.Bí ọwọ́ kò bá wá tẹ olè, ẹni tí ó gba ìṣúra pamọ́ yìí gbọdọ̀ wá sí ilé Ọlọrun kí ó fi Ọlọrun ṣẹ̀rí pé òun kò fi ọwọ́ kan ìṣúra tí aládùúgbò òun fi pamọ́ sí òun lọ́wọ́.Ọ̀kan ninu àwọn àlejò náà wí pé, “Dájúdájú, n óo pada tọ̀ ọ́ wá ní ìwòyí ọdún tí ń bọ̀, Sara, aya rẹ yóo bí ọmọkunrin kan.”Sara fetí mọ́ ògiri lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ lẹ́yìn ibi tí àwọn àlejò náà wà, ó ń gbọ́ gbogbo ohun tí wọ́n ń sọ. nígbà tí Gehasi, iranṣẹ Eliṣa, sọ ninu ara rẹ̀ pé, “Olúwa mi jẹ́ kí Naamani ará Siria yìí lọ láì gba ohun tí ó mú wá lọ́wọ́ rẹ̀. Mo fi OLUWA búra pé, n óo sáré tẹ̀lé e láti gba nǹkan lọ́wọ́ rẹ̀.” The goat did not say it was not sired by the sheep; it was the sheep that said it was not sired by the goat.
nitori pe awon omuti ati awon wobia yoo di talaka,oorun asunju a si maa so eniyan di alakiisa.Bi owo ko ba wa te ole, eni ti o gba isura pamo yii gbodo wa si ile Olorun ki o fi Olorun seri pe oun ko fi owo kan isura ti aladuugbo oun fi pamo si oun lowo.Okan ninu awon alejo naa wi pe, “Dajudaju, n oo pada to o wa ni iwoyi odun ti n bo, Sara, aya re yoo bi omokunrin kan.”Sara feti mo ogiri lenu ona ago leyin ibi ti awon alejo naa wa, o n gbo gbogbo ohun ti won n so. nigba ti Gehasi, iranse Elisa, so ninu ara re pe, “Oluwa mi je ki Naamani ara Siria yii lo lai gba ohun ti o mu wa lowo re. Mo fi OLUWA bura pe, n oo sare tele e lati gba nnkan lowo re.” The goat did not say it was not sired by the sheep; it was the sheep that said it was not sired by the goat.
Mo bá dé Teli Abibu lọ́dọ̀ àwọn ìgbèkùn tí wọn ń gbé ẹ̀bá odò Kebari. Ọjọ́ meje ni mo fi wà pẹlu wọn, tí mo jókòó tì wọ́n, tí mò ń wò wọ́n tìyanu-tìyanu.Wọn á gbàgbé wọn láàrin ìlú,ẹnikẹ́ni kì í ranti orúkọ wọn mọ́,bẹ́ẹ̀ ni ẹni ibi ṣe é wó lulẹ̀ bí ìtì igi.’Ẹ kọ gbogbo òfin wọnyi sára rẹ̀, nígbà tí ẹ bá ń rékọjá lọ láti wọ ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín yóo fun yín, ilẹ̀ tí ó kún fún wàrà ati oyin, gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun àwọn baba yín ti ṣèlérí fun yín. Gbogbo wọn ni wọ́n gbà fún un, ẹnu sì yà wọ́n fún ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ tí ó ń sọ jáde, wọ́n wá ń sọ pé, “Àbí ọmọ Josẹfu kọ́ nìyí ni?”One does not count a pregnancy as a child already delivered.
Mo ba de Teli Abibu lodo awon igbekun ti won n gbe eba odo Kebari. Ojo meje ni mo fi wa pelu won, ti mo jokoo ti won, ti mo n wo won tiyanu-tiyanu.Won a gbagbe won laarin ilu,enikeni ki i ranti oruko won mo,bee ni eni ibi se e wo lule bi iti igi.’E ko gbogbo ofin wonyi sara re, nigba ti e ba n rekoja lo lati wo ile ti OLUWA Olorun yin yoo fun yin, ile ti o kun fun wara ati oyin, gege bi OLUWA Olorun awon baba yin ti seleri fun yin. Gbogbo won ni won gba fun un, enu si ya won fun oro oore-ofe ti o n so jade, won wa n so pe, “Abi omo Josefu ko niyi ni?”One does not count a pregnancy as a child already delivered.
Eégún wọlé, ó ní òun ò rí Ejonto; Ejontó ní, “Àkísà ni, àbí kíní wọlé?”
Eegun wole, o ni oun o ri Ejonto; Ejonto ni, “Akisa ni, abi kini wole?”
Kí ló dé tí o kò fi pa àṣẹ OLUWA mọ? Kí ló dé tí o fi kó ìkógun, tí o sì ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA?”O óo wí pé, “Wọ́n lù mi, ṣugbọn kò dùn mí;wọ́n nà mí, ṣugbọn ń kò mọ̀.Nígbà wo ni n óo tó jí?N óo tún wá ọtí mìíràn mu.”Àjẹgbé nigún ńjẹbọ.
Ki lo de ti o ko fi pa ase OLUWA mo? Ki lo de ti o fi ko ikogun, ti o si se nnkan buruku loju OLUWA?”O oo wi pe, “Won lu mi, sugbon ko dun mi;won na mi, sugbon n ko mo.Nigba wo ni n oo to ji?N oo tun wa oti miiran mu.”Ajegbe nigun njebo.
Ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Nígbà tí àwọn ọmọ yín bá bèèrè lọ́wọ́ àwọn baba wọn ní ọjọ́ iwájú pé báwo ni ti àwọn òkúta wọnyi ti jẹ́ rí? Nítorí náà, ẹ fẹ́ràn àwọn àlejò; nítorí pé ẹ̀yin náà ti jẹ́ àlejò ní ilẹ̀ Ijipti rí. Wọ́n mú Ẹsita lọ sọ́dọ̀ ọba Ahasu-erusi ní ààfin rẹ̀ ní oṣù Tebeti, tíí ṣe oṣù kẹwaa, ní ọdún keje ìjọba rẹ̀. Igbákejì ni Jehosabadi; òun náà ní ọ̀kẹ́ mẹsan-an (180,000) ọmọ ogun tí wọ́n ti dira ogun, lábẹ́ rẹ̀. Omi adágún ò lè gbé màlúù lọ.
O so fun awon omo Israeli pe, “Nigba ti awon omo yin ba beere lowo awon baba won ni ojo iwaju pe bawo ni ti awon okuta wonyi ti je ri? Nitori naa, e feran awon alejo; nitori pe eyin naa ti je alejo ni ile Ijipti ri. Won mu Esita lo sodo oba Ahasu-erusi ni aafin re ni osu Tebeti, tii se osu kewaa, ni odun keje ijoba re. Igbakeji ni Jehosabadi; oun naa ni oke mesan-an (180,000) omo ogun ti won ti dira ogun, labe re. Omi adagun o le gbe maluu lo.
Lẹ́yìn náà, Joabu fọn fèrè ogun, kí wọ́n dáwọ́ ogun jíjà dúró. Àwọn ọmọ ogun Dafidi bá pada lẹ́yìn àwọn ọmọ ogun Israẹli. 86. Ọrò (ìyà) náà yòò ṣẹ lé wọn
Leyin naa, Joabu fon fere ogun, ki won dawo ogun jija duro. Awon omo ogun Dafidi ba pada leyin awon omo ogun Israeli. 86. Oro (iya) naa yoo se le won
lòrí nípa pé wọn ti ṣe àbòsí, wọn
lori nipa pe won ti se abosi, won
kò sì ní lẹ̀ sòrọ.
ko si ni le soro.
87. Wọn kò ha ri ni pé Àwa la ṣe
87. Won ko ha ri ni pe Awa la se
òru fún wọn láti máa sinmi nínú
oru fun won lati maa sinmi ninu
rẹ̀, àti ọsán fún ìríran? Dájúdájú
re, ati osan fun iriran? Dajudaju
Àmì kan fì bẹ nínú ẹ̀yí fún àwọn
Ami kan fi be ninu eyi fun awon
ẹ̀nìyàn tí wọn gbàgbọ lododo.
eniyan ti won gbagbo lododo.
88. Ní ọjò tí a ô fọn fẹ̀rẹ̀, tí ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀
88. Ni ojo ti a o fon fere, ti eru jeje
yòò dà bo àwọn tí n bẹ ní ọrun àti
yoo da bo awon ti n be ni orun ati
àwọn tí n bẹ lòrí ilẹ̀, àyàfi ẹni tí
awon ti n be lori ile, ayafi eni ti
Allah bá f€.. Àti pé olúkúlùkù wọn
Allah ba f€.. Ati pe olukuluku won
yòò wa sí ọdọ Rẹ̀ ní ẹni yẹpẹrẹ.
yoo wa si odo Re ni eni yepere.
89. Ìwọ yòò sì ri àwọn òkẹ̀ nlánlá
89. Iwo yoo si ri awon oke nlanla
tí ìwọ rò pé wọn fi ìdí múlẹ̀ ṣinṣin,
ti iwo ro pe won fi idi mule sinsin,
tí wọn yòò máa rékọjá lọ gẹgẹ bí
ti won yoo maa rekoja lo gege bi
ẹ̀ṣú òjò. Iṣé ọwọ Allah ni, Ẹni tí O
esu ojo. Ise owo Allah ni, Eni ti O
dá. gbogbo. nùkan. ní pípé.
da. gbogbo. nukan. ni pipe.
Dájúdájú Òun jẹ Olùfúnni ní ìrò
Dajudaju Oun je Olufunni ni iro
nípa ohun tí ẹ̀ n ṣe.
nipa ohun ti e n se.
90. Ẹnikẹni tí o bá ṣe rere, yòò gba
90. Enikeni ti o ba se rere, yoo gba
ẹ̀san ẹ̀yí tí 0 dára ju bẹ̀ẹ̀ lọ, àti pẹ̀
esan eyi ti 0 dara ju bee lo, ati pe
àwọn ni WỌn máa ní ìfàyàbalẹ̀
awon ni WOn maa ni ifayabale
kúrò nínú ìpayà ọjọ náà.
kuro ninu ipaya ojo naa.
91. Ẹnikẹni tí ô bá sì ṣe aburú, A ô
91. Enikeni ti o ba si se aburu, A o
dojú wọn bolẹ̀ nínú iná (A Ôô sì wi
doju won bole ninu ina (A Oo si wi
fún wọn pé), 'Njẹ a ô san yín ní
fun won pe), 'Nje a o san yin ni
ẹ̀san mìíràn Ju ohun tí ẹ ṣe lọ?'
esan miiran Ju ohun ti e se lo?'
92. (Wi pé) 'ohun tí a pa mí láṣẹ rẹ̀
92. (Wi pe) 'ohun ti a pa mi lase re
ni pé kí n máa sin Olúwa tí o ni ìlú
ni pe ki n maa sin Oluwa ti o ni ilu
yìí tí Ô ti sọ 6 di mímô. sì ni
yii ti O ti so 6 di mimo. si ni
gbogbo nìkan. A sì tún pa mí láṣẹ
gbogbo nikan. A si tun pa mi lase
lati J$ òkan nínú àwọn tí O ju ara
lati J$ okan ninu awon ti O ju ara
wọn sílẹ̀ (fún Allah);
won sile (fun Allah);
O ti gbé mi ró nítorí ìwà pípé mi,o sì fi ẹsẹ̀ mi múlẹ̀ níwájú rẹ títí lae.Gbogbo ìjọ eniyan Israẹli gbéra láti aṣálẹ̀ Sini, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí lọ láti ibùsọ̀ kan dé ekeji, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún wọn. Wọ́n pàgọ́ sí Refidimu, ṣugbọn kò sí omi fún wọn láti mu. Ẹni tó bá bẹ̀rù OLUWA, yóo kórìíra ibi,mo kórìíra ìwà ìgbéraga, ọ̀nà ibi ati ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́.Àwọn ọmọ Gibari jẹ́ marundinlọgọrun-unÀjàgà wúwo ni baba mi gbé bọ̀ yín lọ́rùn, ṣugbọn tèmi yóo tún wúwo ju ti baba mi lọ. Pàṣán ni baba mi fi nà yín, ṣugbọn àkeekèé ni èmi óo fi ta yín.’ ”Wọ́n bá tún bèèrè pé, “Ó dára, ta ni ọ́? Ó yẹ kí á lè rí èsì mú pada fún àwọn tí wọ́n rán wa wá. Kí ni o sọ nípa ara rẹ?”Ó bí ọgbọ̀n ọmọkunrin, tí wọ́n ń gun ọgbọ̀n kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ọgbọ̀n ìlú ni wọ́n sì tẹ̀dó, tí wọn ń pe orúkọ wọn ní Hafoti Jairi títí di òní olónìí. Wọ́n wà ní ilẹ̀ Gileadi. ti ṣe ẹ̀yí lééwọ." Bí wọn bá jẹrìí,
O ti gbe mi ro nitori iwa pipe mi,o si fi ese mi mule niwaju re titi lae.Gbogbo ijo eniyan Israeli gbera lati asale Sini, won bere si lo lati ibuso kan de ekeji, gege bi ase ti OLUWA pa fun won. Won pago si Refidimu, sugbon ko si omi fun won lati mu. Eni to ba beru OLUWA, yoo koriira ibi,mo koriira iwa igberaga, ona ibi ati oro ibaje.Awon omo Gibari je marundinlogorun-unAjaga wuwo ni baba mi gbe bo yin lorun, sugbon temi yoo tun wuwo ju ti baba mi lo. Pasan ni baba mi fi na yin, sugbon akeekee ni emi oo fi ta yin.’ ”Won ba tun beere pe, “O dara, ta ni o? O ye ki a le ri esi mu pada fun awon ti won ran wa wa. Ki ni o so nipa ara re?”O bi ogbon omokunrin, ti won n gun ogbon ketekete, ogbon ilu ni won si tedo, ti won n pe oruko won ni Hafoti Jairi titi di oni olonii. Won wa ni ile Gileadi. ti se eyi leewo." Bi won ba jerii,
má ṣe bá wọn jẹrìí, kí o má sì ṣe
ma se ba won jerii, ki o ma si se
tẹ̀lé ìfẹ búburú inú àwọn tí wọn
tele ife buburu inu awon ti won
kò gba ọjJỌ ìkẹyìn gbọ àti àwọn tí
ko gba ojJO ikeyin gbo ati awon ti
wọn n bá Olúwa wọn wá ẹgbẹ.
won n ba Oluwa won wa egbe.
ÌDÁ 19
IDA 19
152. Sọ pé; 'Ẹ wá kí n ka àwọn
152. So pe; 'E wa ki n ka awon
nìkan tí Olúwa yín ṣe léẹ̀wọ fún
nikan ti Oluwa yin se leewo fun
yin: (òhun ni) pé kí ẹ má ṣe da
yin: (ohun ni) pe ki e ma se da
nìkan mìíràn pọ mọ Ọn, àti pé
nikan miiran po mo On, ati pe
ki ẹ. máa ṣe rere lẹ̀kùn-ún rẹ̀rẹ
ki e. maa se rere lekun-un rere
fún àwọn òbí, kí ẹ má sì ṣe pa
fun awon obi, ki e ma si se pa
àwọn ọmọ yín nítorí (ìbẹ̀rù) òṣì-
awon omo yin nitori (iberu) osi-
Àwa là fì pẹ̀sṣẹ̀ fún yín àti fún
Awa la fi pesse fun yin ati fun
àwọn náà- kí ẹ má ṣe súnmọ ìwà
awon naa- ki e ma se sunmo iwa
ẹ̀gbin, ẹ̀yí tí ô hàn nínu rẹ̀ àti ẹ̀yí
egbin, eyi ti o han ninu re ati eyi
tí ô pamọ; àti pẹ̀ kí ẹ má ṣe pa
ti o pamo; ati pe ki e ma se pa
ẹ̀mí tí Allah ṣe léẹ̀wò, àyàfi pẹ̀lú
emi ti Allah se leewo, ayafi pelu
ẹ̀tẹ. Eléyìí ní OÔ pa yín láṣẹ rẹ̀, kí
ete. Eleyii ni OO pa yin lase re, ki
ẹ baà lẹ̀ gbọ àgbọyé.
e baa le gbo agboye.
153. 'Ẹ má ṣe súnmọ ohun ìní
153. 'E ma se sunmo ohun ini
ọmọ òrukàn, àyàfi (ní ẹ̀nà) tô
omo orukan, ayafi (ni ena) to
dára jùlọ, títí tí yúò fi bàlágà. Ki
dara julo, titi ti yuo fi balaga. Ki
ẹ sì máa wọn òsùnwòọn àti ìwọn
e si maa won osunwoon ati iwon
pẹ̀lú ìṣẹ̀tò. À kò di ẹrù ru ẹ̀mí kan
pelu iseto. A ko di eru ru emi kan
àyàfi ní ìbàmu pẹ̀lú agbára rẹ̀,
ayafi ni ibamu pelu agbara re,
Nígbà tí ẹ bá sì n sọrọ ẹ ṣe ẹ̀tọ,
Nigba ti e ba si n soro e se eto,
kúdà (kí ẹni tí òô kàn) jẹ ìbátan.
kuda (ki eni ti oo kan) je ibatan.
Kí ẹ sì máa mú màjẹ̀mu (tí ẹ bá)
Ki e si maa mu majemu (ti e ba)
Allah (dá) ṣẹ. Éyí ni O pa láṣẹ
Allah (da) se. Eyi ni O pa lase
fún yín kí ẹ lẹ̀ máa rántí."
fun yin ki e le maa ranti."
154. Tún (wí pé), 'Éyí ni ònà Mi
154. Tun (wi pe), 'Eyi ni ona Mi