diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
(iwájú ìtẹ ìdájọ), Òun yòò wí pé, | (iwaju ite idajo), Oun yoo wi pe, |
Ẹyin ha pe àwọn Àmì Mi nírọ
nígbà ti ìmò yín nípa wọn kò tú
nìkan tàbí kí ni ohun tí ẹ̀ n ṣe? | Eyin ha pe awon Ami Mi niro
nigba ti imo yin nipa won ko tu
nikan tabi ki ni ohun ti e n se? |
Wọ́n gbé òkú Absalomu jù sinu ihò jíjìn kan ninu igbó, wọ́n sì kó ọpọlọpọ òkúta jọ sórí òkú rẹ̀. Gbogbo àwọn ọmọ ogun Israẹli bá sá, olukuluku gba ilé rẹ̀ lọ.Omi ló dànù, agbè ò fọ́. | Won gbe oku Absalomu ju sinu iho jijin kan ninu igbo, won si ko opolopo okuta jo sori oku re. Gbogbo awon omo ogun Israeli ba sa, olukuluku gba ile re lo.Omi lo danu, agbe o fo. |
Gbogbo àwọn wọnyi ni wọ́n wà lábẹ́ ọba ní Jerusalẹmu, láìka àwọn tí ó fi sí àwọn ìlú olódi ní gbogbo ilẹ̀ Juda.Ọba fẹ́ràn rẹ̀ ju gbogbo àwọn obinrin yòókù lọ, ó sì rí ojurere ọba ju gbogbo àwọn wundia yòókù lọ. Ọba gbé adé lé e lórí, ó sì fi ṣe ayaba dípò Faṣiti. A máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn opó. Ó fẹ́ràn àwọn àlejò, a sì máa fún wọn ní oúnjẹ ati aṣọ. Joṣua bá to àwọn òkúta mejila tí wọ́n kó jáde láti inú odò Jọdani kalẹ̀ ní Giligali. Ajé sọ ọmọ nù bí òkò. | Gbogbo awon wonyi ni won wa labe oba ni Jerusalemu, laika awon ti o fi si awon ilu olodi ni gbogbo ile Juda.Oba feran re ju gbogbo awon obinrin yooku lo, o si ri ojurere oba ju gbogbo awon wundia yooku lo. Oba gbe ade le e lori, o si fi se ayaba dipo Fasiti. A maa se idajo otito fun awon alainibaba ati awon opo. O feran awon alejo, a si maa fun won ni ounje ati aso. Josua ba to awon okuta mejila ti won ko jade lati inu odo Jodani kale ni Giligali. Aje so omo nu bi oko. |
O óo dàbí ẹni tí ó dùbúlẹ̀ lórí agbami òkun,bí ẹni tí ó sùn lórí òpó ọkọ̀.Eegun àjànàkú: ó há ìkokò lẹ́nu. | O oo dabi eni ti o dubule lori agbami okun,bi eni ti o sun lori opo oko.Eegun ajanaku: o ha ikoko lenu. |
Ó sì rán ọ jáde pẹlu àṣẹ pé kí o pa gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ará Amaleki run. Ó ní kí o gbógun tì wọ́n títí o óo fi pa wọ́n run patapata. Ó sọ fún wọn pé, “Ní òtítọ́ ẹ lè pa òwe yìí fún mi pé, ‘Oníṣègùn, wo ara rẹ sàn! Ohun gbogbo tí a gbọ́ pé o ṣe ní Kapanaumu, ṣe wọ́n níhìn-ín, ní ìlú baba rẹ.’ ” Wọ́n ń jẹ oúnjẹ àgàn tí kò bímọ,wọn kò sì ṣe rere fún opó.Nígbà náà ni ẹ̀mí gbé mi dìde, ó sì gbé mi lọ. Tìbínú-tìbínú ni mo sì fi ń lọ. Ẹ̀mí OLUWA ni ó gbé mi lọ pẹlu agbára. Ní ọjọ́ tí ẹ bá kọjá odò Jọdani, tí ẹ bá ti wọ inú ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín yóo fun yín, ẹ to òkúta ńláńlá jọ kí ẹ fi ohun tí wọ́n fi ń rẹ́ ilé rẹ́ ẹ. Ó bá sáré tẹ̀lé Naamani. Nígbà tí Naamani rí i pé ẹnìkan ń sáré bọ̀, ó sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ̀kẹ́ ogun tí ó gùn láti pàdé rẹ̀, ó bèèrè pé, “Ṣé kò sí nǹkan?”If sired by a goat, one does not go foraging in the realm of sheep. | O si ran o jade pelu ase pe ki o pa gbogbo awon elese, ara Amaleki run. O ni ki o gbogun ti won titi o oo fi pa won run patapata. O so fun won pe, “Ni otito e le pa owe yii fun mi pe, ‘Onisegun, wo ara re san! Ohun gbogbo ti a gbo pe o se ni Kapanaumu, se won nihin-in, ni ilu baba re.’ ” Won n je ounje agan ti ko bimo,won ko si se rere fun opo.Nigba naa ni emi gbe mi dide, o si gbe mi lo. Tibinu-tibinu ni mo si fi n lo. Emi OLUWA ni o gbe mi lo pelu agbara. Ni ojo ti e ba koja odo Jodani, ti e ba ti wo inu ile ti OLUWA Olorun yin yoo fun yin, e to okuta nlanla jo ki e fi ohun ti won fi n re ile re e. O ba sare tele Naamani. Nigba ti Naamani ri i pe enikan n sare bo, o sokale lori keke ogun ti o gun lati pade re, o beere pe, “Se ko si nnkan?”If sired by a goat, one does not go foraging in the realm of sheep. |
Abrahamu ati Sara ti di àgbàlagbà ní àkókò yìí, ogbó ti dé sí wọn, ọjọ́ ti pẹ́ tí Sara ti rí nǹkan oṣù rẹ̀ kẹ́yìn. “Nígbàkúùgbà tí ohun ìní bá di àríyànjiyàn láàrin eniyan meji, kì báà jẹ́ mààlúù, tabi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, tabi aguntan, tabi aṣọ, tabi ohunkohun tí ó bá ti sọnù, tí ó sì di àríyànjiyàn, àwọn mejeeji tí wọn ń lọ́ nǹkan mọ́ ara wọn lọ́wọ́ gbọdọ̀ wá sí ilé Ọlọrun, kí wọ́n sì fi Ọlọrun ṣẹ̀rí, ẹni tí Ọlọrun bá dá lẹ́bi yóo san ìlọ́po meji nǹkan náà fún ẹnìkejì rẹ̀.Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di aláìníbaba,kí aya rẹ̀ di opó.OLUWA bá rán Jerubaali ati Baraki, ati Jẹfuta ati èmi, Samuẹli, láti gbà yín lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá yín káàkiri, ó sì jẹ́ kí ẹ wà ní alaafia. Alufaa yóo sì máa wọ́n ẹ̀jẹ̀ wọn sí ara pẹpẹ OLUWA lẹ́nu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ, yóo sì sun ọ̀rá wọn bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn sí OLUWA. Ẹjọ́ tí wọ́n bá dá fun yín ni kí ẹ gbà, kí ẹ sì tẹ̀lé gbogbo ìlànà tí wọ́n bá là sílẹ̀. Ẹ kò gbọdọ̀ yà sí ọ̀tún tabi sí òsì ninu ẹjọ́ tí wọ́n bá dá fun yín. Wọ́n ń fi oríṣìíríṣìí ife wúrà mu ọtí, ọba sì pèsè ọtí lọpọlọpọ gẹ́gẹ́ bí ipò ọlá ńlá rẹ̀. Àwọn ọkunrin náà bá gbé ẹ̀bùn náà, wọ́n sì mú ìlọ́po meji owó tí wọ́n nílò, ati Bẹnjamini, wọ́n lọ siwaju Josẹfu ní Ijipti. 147. Àti fún àwọn Yahudi ni a ṣe | Abrahamu ati Sara ti di agbalagba ni akoko yii, ogbo ti de si won, ojo ti pe ti Sara ti ri nnkan osu re keyin. “Nigbakuugba ti ohun ini ba di ariyanjiyan laarin eniyan meji, ki baa je maaluu, tabi ketekete, tabi aguntan, tabi aso, tabi ohunkohun ti o ba ti sonu, ti o si di ariyanjiyan, awon mejeeji ti won n lo nnkan mo ara won lowo gbodo wa si ile Olorun, ki won si fi Olorun seri, eni ti Olorun ba da lebi yoo san ilopo meji nnkan naa fun enikeji re.Ki awon omo re di alainibaba,ki aya re di opo.OLUWA ba ran Jerubaali ati Baraki, ati Jefuta ati emi, Samueli, lati gba yin lowo awon ota yin kaakiri, o si je ki e wa ni alaafia. Alufaa yoo si maa won eje won si ara pepe OLUWA lenu ona Ago Ajo, yoo si sun ora won bi ebo sisun olooorun didun si OLUWA. Ejo ti won ba da fun yin ni ki e gba, ki e si tele gbogbo ilana ti won ba la sile. E ko gbodo ya si otun tabi si osi ninu ejo ti won ba da fun yin. Won n fi orisiirisii ife wura mu oti, oba si pese oti lopolopo gege bi ipo ola nla re. Awon okunrin naa ba gbe ebun naa, won si mu ilopo meji owo ti won nilo, ati Benjamini, won lo siwaju Josefu ni Ijipti. 147. Ati fun awon Yahudi ni a se |
gbogbo ẹran eléẹ̀kánná léẹ̀wò; | gbogbo eran eleekanna leewo; |
bakan náà ni A ṣe ọrá àwọn | bakan naa ni A se ora awon |
ewúrẹ léẹ̀wọ fún wọn, àyàfi ẹ̀yí tí | ewure leewo fun won, ayafi eyi ti |
ẹ̀yin wọn bá rù tàbí ìfun, tàbí ẹ̀yi | eyin won ba ru tabi ifun, tabi eyi |
tô rò pò mQ egungun. Éyí ni ẹ̀san | to ro po mQ egungun. Eyi ni esan |
ti A fún wọn nítorí òbìlẹ̀jẹ wọn. | ti A fun won nitori obileje won. |
Ní dájúdájú ni A sì jẹ olôdodo. | Ni dajudaju ni A si je olododo. |
148. Ṣùgbọn bí wọn ba pò ọ ní | 148. Sugbon bi won ba po o ni |
òpùrọ, nígbà náà sọ pé, 'Olúwa | opuro, nigba naa so pe, 'Oluwa |
yín jẹ A láàánú tí ô gbòòrò, bẹ̀ẹ̀ ni | yin je A laaanu ti o gbooro, bee ni |
a kì yòô yí ìbínu Rẹ̀ padà kúrò | a ki yoo yi ibinu Re pada kuro |
fún àwọn tô jẹ̀bi. | fun awon to jebi. |
149. Àwọn tò nì bá Allah wá ẹgbé | 149. Awon to ni ba Allah wa egbe |
yòò máa sọ pé, 'Bí oô bá wu | yoo maa so pe, 'Bi oo ba wu |
Allah ni, àwa ìbá tí bá A wá | Allah ni, awa iba ti ba A wa |
ẹgbẹ, àti àwọn bàbá wa pẹ̀lú; bẹ̀ẹ̀ | egbe, ati awon baba wa pelu; bee |
ni àwa ìbá tí ṣe kiní kan léẹ̀wò." | ni awa iba ti se kini kan leewo." |
Lọnà kan. náà ni àwọn t0 ṣíwáju | Lona kan. naa ni awon t0 siwaju |
wọn pe (àwọn Òjíṣẹ, Allah) | won pe (awon Ojise, Allah) |
lopùrọ, títí ti wọn fi tọ ìbínú Wa | lopuro, titi ti won fi to ibinu Wa |
wò. Sọ pé; 'Njẹ ẹ ní ìmọ kankan? | wo. So pe; 'Nje e ni imo kankan? |
TO ba rí bẹ̀ẹ̀ ẹ mú un wá fún wa. | TO ba ri bee e mu un wa fun wa. |
Ẹ kò tẹ̀lé nìkan kan bí kò ṣe | E ko tele nikan kan bi ko se |
àrÒSỌ- (lasán). Ẹ kò sì ṣe | arOSO- (lasan). E ko si se |
ohunkQhun àyàfi irọ. | ohunkQhun ayafi iro. |
150.. Sọ pé: 'Ti Allah ni ìdí ẹ̀rọ | 150.. So pe: 'Ti Allah ni idi ero |
tò yẹ̀ kooro.. Tí ô bá ṣe pé Ô fé | to ye kooro.. Ti o ba se pe O fe |
ni, Òun ìbá ti fi gbogbo yín | ni, Oun iba ti fi gbogbo yin |
mọònà.' | moona.' |
151. Sọ pé: 'Ẹ mú àwọn ẹlẹrìí | 151. So pe: 'E mu awon elerii |
yin wá tí wọn yòò Jẹrìí pé Allah | yin wa ti won yoo Jerii pe Allah |
Àfi Kalebu ọmọ Jefune, ọmọ Kenisi ati Joṣua ọmọ Nuni, nítorí pé wọ́n fi tọkàntọkàn ṣe tèmi. Ó gbé àpótí ẹ̀rí náà sinu àgọ́ náà, ó sì ta aṣọ ìbòjú rẹ̀ dí i gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.Nígbà tí Jairi ṣaláìsí, wọ́n sin ín sí ilẹ̀ Kamoni.Àwọn ọmọ Bẹtilẹhẹmu jẹ́ mẹtalelọgọfa (123)Èmi, ọgbọ́n, òye ni mò ń bá gbélé,mo ṣe àwárí ìmọ̀ ati làákàyè.Ó bá dáhùn gẹ́gẹ́ bí wolii Aisaya ti sọ pé:“Èmi ni ‘ohùn ẹni tí ń kígbe ninu aṣálẹ̀ pé:Ẹ ṣe ọ̀nà tí ó tọ́ fún Oluwa.’ ” Àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ sọ fún un pé, “Lọ sọ fún wọn pé, ‘Ìka ọwọ́ mi tí ó kéré jù yóo tóbi ju ẹ̀gbẹ́ baba mi lọ. Ìdí rẹ̀ ni pé, Dafidi ṣe ohun tí ó dára lójú OLUWA, kò sì ṣàìgbọràn sí àṣẹ rẹ̀ rí ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, (àfi ohun tí ó ṣe sí Uraya ará Hiti). bí àwọn eniyan mi, tí à ń fi orúkọ mi pè, bá rẹ ara wọn sílẹ̀, tí wọ́n bá gbadura, tí wọ́n sì wá ojurere mi, tí wọ́n bá yipada kúrò ní ọ̀nà burúkú wọnyi; n óo gbọ́ láti ọ̀run, n óo dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, n óo sì wo ilẹ̀ wọn sàn. Nígbà tí àkókò ọ̀fọ̀ rẹ̀ parí, Dafidi ní kí wọ́n mú un wá sí ààfin, Batiṣeba sì di aya rẹ̀. Ó bí ọmọkunrin kan fún un, ṣugbọn inú OLUWA kò dùn sí ohun tí Dafidi ṣe.Mose kò sì lè wọ inú rẹ̀ nítorí ìkùukùu tí ó wà lórí rẹ̀, ati pé ògo OLUWA kún inú rẹ̀. lôrí, nígbà tí Òdn tí ṣe àlàyé | Afi Kalebu omo Jefune, omo Kenisi ati Josua omo Nuni, nitori pe won fi tokantokan se temi. O gbe apoti eri naa sinu ago naa, o si ta aso iboju re di i gege bi OLUWA ti pase fun un.Nigba ti Jairi salaisi, won sin in si ile Kamoni.Awon omo Betilehemu je metalelogofa (123)Emi, ogbon, oye ni mo n ba gbele,mo se awari imo ati laakaye.O ba dahun gege bi wolii Aisaya ti so pe:“Emi ni ‘ohun eni ti n kigbe ninu asale pe:E se ona ti o to fun Oluwa.’ ” Awon egbe re so fun un pe, “Lo so fun won pe, ‘Ika owo mi ti o kere ju yoo tobi ju egbe baba mi lo. Idi re ni pe, Dafidi se ohun ti o dara loju OLUWA, ko si saigboran si ase re ri ni gbogbo ojo aye re, (afi ohun ti o se si Uraya ara Hiti). bi awon eniyan mi, ti a n fi oruko mi pe, ba re ara won sile, ti won ba gbadura, ti won si wa ojurere mi, ti won ba yipada kuro ni ona buruku wonyi; n oo gbo lati orun, n oo dari ese won ji won, n oo si wo ile won san. Nigba ti akoko ofo re pari, Dafidi ni ki won mu un wa si aafin, Batiseba si di aya re. O bi omokunrin kan fun un, sugbon inu OLUWA ko dun si ohun ti Dafidi se.Mose ko si le wo inu re nitori ikuukuu ti o wa lori re, ati pe ogo OLUWA kun inu re. lori, nigba ti Odn ti se alaye |
àwọn nìkan tí O ṣe léẹ̀wò fún | awon nikan ti O se leewo fun |
yin- àyàfi ẹ̀yí tí ìnira bá mú yín | yin- ayafi eyi ti inira ba mu yin |
ṣe? Àti pé dájúdájú òpọlọpọ lò fi | se? Ati pe dajudaju opolopo lo fi |
ṣi (àwọn elòmíràn) lọnà pẹ̀lú ẹ̀rò | si (awon elomiran) lona pelu ero |
búburú - wọn... àìmẹ̀. | buburu - won... aime. |
Dájúdájú, Olúwa rẹ mọ àwọn | Dajudaju, Oluwa re mo awon |
olùrékọjá ẹnu ààlà. | olurekoja enu aala. |
121. Kí ẹ sì yẹra fún àwọn ẹ̀ṣẹ̀ to | 121. Ki e si yera fun awon ese to |
hàn àti ẹ̀yí tí 0 pamọ. Dájúdájú, | han ati eyi ti 0 pamo. Dajudaju, |
ní ti àwọn (tô n ṣe iṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ a ô san | ni ti awon (to n se ise ese a o san |
wọn lẹsan ohun tí wọn n ṣe. | won lesan ohun ti won n se. |
122. Ẹyin kò sì gbọdọ jẹ nínú | 122. Eyin ko si gbodo je ninu |
ohun tí a kò dárúkọ Allah lé lòrí, | ohun ti a ko daruko Allah le lori, |
dájúdájú ẹ̀yí j€ ìwà àìgbọràn. Àti | dajudaju eyi j€ iwa aigboran. Ati |
pé àwọn elẹ̀ṣù ẹ̀nìyàn a máa fi | pe awon elesu eniyan a maa fi |
ẹ̀rò búburú sí ọkàn àwọn ọrẹ wọn | ero buburu si okan awon ore won |
kí wọn lẹ̀ máa bá yín jiyàn. Bí | ki won le maa ba yin jiyan. Bi |
ẹ̀yin ba wa tẹ̀ lé wọn, dájúdájú | eyin ba wa te le won, dajudaju |
ẹ̀yin náà yúòò máa wá orogún | eyin naa yuoo maa wa orogun |
(pẹ̀lú Ọlọrun). | (pelu Olorun). |
ÌDÁ 15 | IDA 15 |
123. Njẹ ẹni tí ò ti j€ òkú, tí a sì sọ | 123. Nje eni ti o ti j€ oku, ti a si so |
di alààyẹ̀, tí a sì ṣe ìmọlẹ̀ tí yôòò máa | di alaaye, ti a si se imole ti yooo maa |
fi rìn láàrin àwọn ẹ̀nìyàn fún un a lẹ̀ | fi rin laarin awon eniyan fun un a le |
dà bí ẹni ti ô wà nínú òkùnkùn | da bi eni ti o wa ninu okunkun |
birimùbirimù tí kò sí ònà tí yòò gbà | birimubirimu ti ko si ona ti yoo gba |
jáde nínú rẹ̀? Báyìí ni a ṣe ìṣesí àwọn | jade ninu re? Bayii ni a se isesi awon |
aláìgbàgbọ lọṣọọ lôjú wọn. | alaigbagbo losoo loju won. |
124. Àti pé báyìí ni A fún. àwọn | 124. Ati pe bayii ni A fun. awon |
olòrí nínú àwọn. ẹlẹ̀ṣẹ̀ inú ìlú | olori ninu awon. elese inu ilu |
kọọkan láti máa pẹ̀te (tako òdodo); | kookan lati maa pete (tako ododo); |
wọn kò sì pẹ̀te sí ohunkohun àyàfi | won ko si pete si ohunkohun ayafi |
sí ẹ̀mí ara wọn; ṣùgbọn wọn kò | si emi ara won; sugbon won ko |
Ó sọ fún Solomoni ọba pé, “Kò sí irọ́ ninu gbogbo ohun tí mo ti gbọ́ nípa rẹ ati nípa ọgbọ́n rẹ. Ìjọba Tanzania fi Ajìjàgbara Ọmọ Orílẹ̀-èdèe Uganda sí àtìmọ́lé, wọ́n sì lé e kúrò nílùú | O so fun Solomoni oba pe, “Ko si iro ninu gbogbo ohun ti mo ti gbo nipa re ati nipa ogbon re. Ijoba Tanzania fi Ajijagbara Omo Orile-edee Uganda si atimole, won si le e kuro niluu |
Wairagala Wakabi, àgbà ọ̀jẹ̀ ajàfẹ́tọ̀ọ́ ẹ̀rọ ayárabíàṣá tí ó wá láti Uganda, di ẹni àtìmọ́lé ní Pápákọ̀ òfuurufú Julius Nyerere International Airport ní Dar es Salaam, Tanzania lọ́jọ́ 25 oṣù Igbe. | Wairagala Wakabi, agba oje ajafetoo ero ayarabiasa ti o wa lati Uganda, di eni atimole ni Papako ofuurufu Julius Nyerere International Airport ni Dar es Salaam, Tanzania lojo 25 osu Igbe. |
A fi ìwé pe Wakabi kí ó wá á sọ̀rọ̀ níbi ètò Àyájọ́ Àwọn Olùgbèjà Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ní Tanzania ọlọ́dọọdún tí Àgbáríjọ Olùgbèjà Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Tanzania (THRDC) jẹ́ olùgbàlejò. Wakabi ni Olùdarí Àgbà Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ètò-ìmúlò Ìmọ̀-ẹ̀rọ Gbogboògbò fún Ìlà-Oòrùn àti Gúúsù Ilẹ̀ Adúláwò (CIPESA), ọ̀kan gbòógì nínú ilé-iṣẹ́ tí ó ń ṣe ètò tí ó dá lórí ètò-ìmúlò ẹ̀rọ ayélujára àti òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ ní orí ayélujára ní ilẹ̀ Adúláwò. | A fi iwe pe Wakabi ki o wa a soro nibi eto Ayajo Awon Olugbeja Eto Omoniyan ni Tanzania olodoodun ti Agbarijo Olugbeja Eto Omoniyan ti Tanzania (THRDC) je olugbalejo. Wakabi ni Oludari Agba Ifowosowopo Eto-imulo Imo-ero Gbogboogbo fun Ila-Oorun ati Guusu Ile Adulawo (CIPESA), okan gboogi ninu ile-ise ti o n se eto ti o da lori eto-imulo ero ayelujara ati ominira oro siso ni ori ayelujara ni ile Adulawo. |
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí tí a fi ọ̀rọ̀ wá Wakabi lẹ́nu wò, tí wọn kò sì jẹ́ kí ó rí agbẹjọ́rò, a dá a padà sí Uganda. | Leyin opolopo wakati ti a fi oro wa Wakabi lenu wo, ti won ko si je ki o ri agbejoro, a da a pada si Uganda. |
Àwọn aṣojú láti Àgbáríjọ Olùgbèjà Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn gbìyànjú láti jà fún un, àmọ́ a sọ fún wọn wípé fún “àǹfààní ìlú” ni a fi dá Wakabi padà sí ìlúu rẹ̀: | Awon asoju lati Agbarijo Olugbeja Eto Omoniyan gbiyanju lati ja fun un, amo a so fun won wipe fun “anfaani ilu” ni a fi da Wakabi pada si iluu re: |
Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ìṣẹ̀lẹ̀ náà kò ju wákàtí díẹ̀ lọ, ó mú ìjáyà ńlá bá àwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ ní agbègbè náà, tí ọ̀ràn ìwà àìtọ́ tí orílẹ̀-èdèe Tanzania ń wù sí àwọn ajìjàgbara àti oníṣẹ́-ìròyìn ń peléke sí i. Nínú oṣù Belu ọdún tí ó ré kọjá, àwọn òṣìṣẹ́ Ìgbìmọ̀ tí ó ń Dáàbò bo Oníṣẹ́-ìròyìn, Angela Quintal àti Muthoki Mumo di ẹni àtìmọ́lé fún ọ̀pọ̀ wákàtí ní Dar es Salaam, Tanzania, tí ìwé ẹ̀rí ọmọ-ìlú-fún-ìrìnnàa wọ́n di gbígbà lọ́wọ́ọ wọn. | Bi o ti le je pe isele naa ko ju wakati die lo, o mu ijaya nla ba awon ajafetoo ni agbegbe naa, ti oran iwa aito ti orile-edee Tanzania n wu si awon ajijagbara ati onise-iroyin n peleke si i. Ninu osu Belu odun ti o re koja, awon osise Igbimo ti o n Daabo bo Onise-iroyin, Angela Quintal ati Muthoki Mumo di eni atimole fun opo wakati ni Dar es Salaam, Tanzania, ti iwe eri omo-ilu-fun-irinnaa won di gbigba lowoo won. |
Human Rights Watch sọ wípé lábẹ́ ìṣàkóso ìjọba Ààrẹ John Magufuli Tanzania ti rí “ìrésílẹ̀ ìbọ̀wọ̀ fún òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ, ìkẹ́gbẹ́ àti àpéjọ dé ojú àmì” | Human Rights Watch so wipe labe isakoso ijoba Aare John Magufuli Tanzania ti ri “iresile ibowo fun ominira oro siso, ikegbe ati apejo de oju ami” |
Ní ọdún-un 2015, Orílẹ̀èdè Olómìnira Ìṣọ̀kan Tanzania kéde Ìgbésẹ̀ Ìrúfin Orí Ẹ̀rọ Ayélujára. Ní àárín ọdún kan tí a kéde òfin yẹn, ó ti tó bí ọmọ orílẹ̀ èdèe Tanzania 14 tí òfín ti mú tí a sì ti dálẹ́jọ́ lábẹ́ òfin fún pé wọ́n sọ̀rọ̀ mọ́ṣààsí sí ààrẹ lórí ẹ̀rọ alátagbà. Pẹ́pẹ́yẹ gbé ọmọ pọ̀n nínú oṣù Ẹrẹ́nà ọdún-un 2018 nígbàtí a gba Ìlànà Ẹ̀rọ Ayárabíàṣá (Ohun orí ayélujára) àti Ìtàkùrọ̀sọ Ìfìwéránṣẹ́ wọlé tí ó mú un ní túláàsì fún àwọn akọbúlọ́ọ̀gù láti fi orúkọ sílẹ̀ tí wọ́n á sì san owó orí tí ó tó bíi US $900 lọ́dún kí wọn ó tó lè gbé àtẹ̀jáde sí orí ayélujára. Èyí mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ búlọ́ọ̀gù aládàádúró ó wọ òkùnkùn. | Ni odun-un 2015, Orileede Olominira Isokan Tanzania kede Igbese Irufin Ori Ero Ayelujara. Ni aarin odun kan ti a kede ofin yen, o ti to bi omo orile edee Tanzania 14 ti ofin ti mu ti a si ti dalejo labe ofin fun pe won soro mosaasi si aare lori ero alatagba. Pepeye gbe omo pon ninu osu Erena odun-un 2018 nigbati a gba Ilana Ero Ayarabiasa (Ohun ori ayelujara) ati Itakuroso Ifiweranse wole ti o mu un ni tulaasi fun awon akobuloogu lati fi oruko sile ti won a si san owo ori ti o to bii US $900 lodun ki won o to le gbe atejade si ori ayelujara. Eyi mu ki opolopo buloogu aladaaduro o wo okunkun. |
Ìpalẹ́numọ́ iléeṣẹ́ akọ̀ròyìn aládàádúró nípasẹ̀ àwọn àdàlù ìṣíwèé fún ilé iṣẹ́ akọ̀ròyìn àti ìrókẹ́kẹ́ mọ́ oníṣẹ́-ìròyìn ti di ìdẹ́rùbà, ìkóra-ẹni-ní-ìjánu àti ìbẹ̀rù láti sọ èrò ọkàn ẹni nípa àwọn olórí orílẹ̀ èdè náà. | Ipalenumo ileese akoroyin aladaaduro nipase awon adalu isiwee fun ile ise akoroyin ati irokeke mo onise-iroyin ti di ideruba, ikora-eni-ni-ijanu ati iberu lati so ero okan eni nipa awon olori orile ede naa. |
Àtìmọ́lé àti ìdápadà Wakabi sí Uganda jẹ́ ìtẹ̀síwájú ìdojú-ìjà-kọ òmìnira ọ̀rọ̀ tòun èrò ọkàn ẹni ní Tanzania. | Atimole ati idapada Wakabi si Uganda je itesiwaju idoju-ija-ko ominira oro toun ero okan eni ni Tanzania. |
Burundi: Kọ Ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ kí o wẹ̀wọ̀n | Burundi: Ko Ikokuko sori aworan Aare ki o wewon |
Akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́fà di ẹni àtìmọ́lé lọjọ́ Ìṣẹ́gun 12, oṣù Ẹrẹ́nà ní agbègbè Kirundo ní Àríwá Ìlà-oòrùn Burundi fún ẹ̀sùn-un kíkọ ìkọkúkọ sórí àwòrán Ààrẹ Pierre Nkurunziza nínú àwọn ìwé ìkọ́ni márùn-ún. Wọ́n fi ẹ̀sùn “títa àbùkù bá Ààrẹ orílẹ̀-èdè” kàn àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà. | Akekoo mefa di eni atimole lojo Isegun 12, osu Erena ni agbegbe Kirundo ni Ariwa Ila-oorun Burundi fun esun-un kiko ikokuko sori aworan Aare Pierre Nkurunziza ninu awon iwe ikoni marun-un. Won fi esun “tita abuku ba Aare orile-ede” kan awon akekoo naa. |
Ẹgbẹ́ Àwọn Àjọ tí ó ń ṣe Àmójútó ìwàlálàáfíà Àwọn ọmọdé ní Burundi jábọ̀ pé wọ́n ti fi akẹ́kọ̀ọ́ kan tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlá sílẹ̀ lẹ́sẹkẹsẹ̀ nítorí pé ó ṣì kéré, kò sì tí ì tó ọdún mẹ́ẹ̀dógún. | Egbe Awon Ajo ti o n se Amojuto iwalalaafia Awon omode ni Burundi jabo pe won ti fi akekoo kan ti o je omo odun metala sile lesekese nitori pe o si kere, ko si ti i to odun meedogun. |
Wọ́n jábọ̀ pé wọ́n ṣe ìdásílẹ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta lọ́jọ́ Ẹtì, 15 oṣù Ẹrẹ́nà ṣùgbọ́n àwọn mẹ́ta yòókù ṣì wà ní àtìmọ́lé. Àwọn ọmọ náà tí wọn kò ju ọmọ ọdún 15 sí 17 yóò ṣe ẹ̀wọ̀n ọdún márùn-ún bí wọ́n bá jẹ̀bi ẹ̀sùn ìtàbùkù bá Ààrẹ orílẹ̀-èdè. Ìwé ìròyìn iwacu jábọ̀ pé àwọn ìdílé tí ọ̀rọ̀ náà kàn wà nínú ìdààmú gidi. | Won jabo pe won se idasile awon akekoo meta lojo Eti, 15 osu Erena sugbon awon meta yooku si wa ni atimole. Awon omo naa ti won ko ju omo odun 15 si 17 yoo se ewon odun marun-un bi won ba jebi esun itabuku ba Aare orile-ede. Iwe iroyin iwacu jabo pe awon idile ti oro naa kan wa ninu idaamu gidi. |
“Ìkọkúkọ [lórí àwòrán Ààrẹ] jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí ó mú ìjìyà dání lábẹ́ òfin ilẹ̀ Burundi gẹ́gẹ́ bí àbọ̀ ìwádìí Reuters kan ṣe sọ. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọjọ́-orí àwọn ọ̀daràn náà lè jẹ́ ìdí fún ṣíṣe àdínkù ìjìyà ẹ̀sẹ̀ nínú ìgbẹ́jọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí. | “Ikokuko [lori aworan Aare] je ese ti o mu ijiya dani labe ofin ile Burundi gege bi abo iwadii Reuters kan se so. Bi o tile je pe ojo-ori awon odaran naa le je idi fun sise adinku ijiya ese ninu igbejo awon akekoo yii. |
Gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ kan tí kò dárúkọ araa rẹ̀ ṣe sọ, wọn kò yẹ àwọn ìwé ìkọ́ni wọ̀nyí wò fún àìmọye ọdún, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sì máa ń pín in lò ni, fún ìdí èyí ó nira láti mọ ẹni tí ó kọ nǹkan sí i ní pàtó. | Gege bi oluko kan ti ko daruko araa re se so, won ko ye awon iwe ikoni wonyi wo fun aimoye odun, awon akekoo si maa n pin in lo ni, fun idi eyi o nira lati mo eni ti o ko nnkan si i ni pato. |
Ìṣẹ̀lẹ̀ tó fara jọ èyí ṣẹlẹ̀ ní 2016, lẹ́yìnin rògbòdìyàn sáà kẹ́ta Ààrẹ náà, nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́ kọ ìkọkúkọ sórí àwòrán (Ààrẹ) Nkurunziza nínú ìwé ìkọ́ni. Àwọn aláṣẹ rí èyí gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀sí gidi tí wọ́n sì lé ọgọọgọ̀rún akẹ́kọ̀ọ́ kúrò ní àwọn ilé ẹ̀kọ́ lóríṣìíríṣi káàkiri orílẹ̀-èdè náà. Akẹ́kọ̀ọ́ mọ́kànlá ni wọ́n fẹ̀sùn ìtàbùkù bá adarí ìlú àti “ìhàlẹ̀ mọ́ ààbò ìlú” kàn, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n padà dá wọn sílẹ̀. | Isele to fara jo eyi sele ni 2016, leyinin rogbodiyan saa keta Aare naa, nigba ti awon akekoo nile eko ko ikokuko sori aworan (Aare) Nkurunziza ninu iwe ikoni. Awon alase ri eyi gege bi iwosi gidi ti won si le ogoogorun akekoo kuro ni awon ile eko lorisiirisi kaakiri orile-ede naa. Akekoo mokanla ni won fesun itabuku ba adari ilu ati “ihale mo aabo ilu” kan, bi o tile je pe won pada da won sile. |
Wọ́n bu ẹnu àtẹ́ lu ìwà yìí gidigidi. Zeid Ra'ad Al Hussein, tí ó jẹ́ aṣàkóso fún ẹ̀ka ìjàfẹ́tọ̀ọ́ ènìyàn lábẹ́ United Nations gbé àkọsílẹ̀ kan jáde ní 29, oṣù Òkúdù 2016: | Won bu enu ate lu iwa yii gidigidi. Zeid Ra'ad Al Hussein, ti o je asakoso fun eka ijafetoo eniyan labe United Nations gbe akosile kan jade ni 29, osu Okudu 2016: |
Ẹ̀rù ń bà mí pẹ̀lú àwọn ìròyìn tí mò ń gbọ́ nípa lílé tí wọ́n ń lé àwọn ọmọ ní ilé-ẹ̀kọ́ àti bí wọ́n ṣe ń tì wọ́n mọ́lé nítorí ìkọkúkọ tí wọ́n kọ sórí àwòrán Ààrẹ nínú àwọn ìwé ìkọ́ni. | Eru n ba mi pelu awon iroyin ti mo n gbo nipa lile ti won n le awon omo ni ile-eko ati bi won se n ti won mole nitori ikokuko ti won ko sori aworan Aare ninu awon iwe ikoni. |
Pierre Nkurunziza ti jẹ ààrẹ ilẹ̀ Burundi láti ọdún 2005. Ní ọdún 2015, àwọn ẹgbẹ́ òṣèlúu rẹ̀ tún gbé e sípò fún sáà kẹ́ta lórí oyè. | Pierre Nkurunziza ti je aare ile Burundi lati odun 2005. Ni odun 2015, awon egbe oseluu re tun gbe e sipo fun saa keta lori oye. |
Ní oṣù Ẹrẹ́nà ọdún tó kọjá, Nkurunziza gba orúkọ tuntun lọ́dọ̀ àwọn ẹgbẹ́ òṣèlúu rẹ̀, Àjọ Agbèjà Òmìnira Àwọn Ológun – Fún Ìgbéga Ìjọba Oníbò (CNDD-FDD). Wọ́n pè é ní “adarí ayérayé tó ga jù”. | Ni osu Erena odun to koja, Nkurunziza gba oruko tuntun lodo awon egbe oseluu re, Ajo Agbeja Ominira Awon Ologun – Fun Igbega Ijoba Onibo (CNDD-FDD). Won pe e ni “adari ayeraye to ga ju”. |
Akọ̀wé gbogboògbò fún CNDD-FDD, Evariste Ndayishimiye ṣàlàyé ìdí tí orúkọ náà ṣe di ti Nkurunziza: | Akowe gbogboogbo fun CNDD-FDD, Evariste Ndayishimiye salaye idi ti oruko naa se di ti Nkurunziza: |
Olùdaríi wa ni, kò sí eni tí a lè fi wé e nínú ẹgbẹ́ẹ wa. Òun ni òbíi wa, òun ni ó ń gbà wá nímọ̀ràn. Ìdí nìyí tí mo ṣe ní kí gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ pọ́n ọn lé nítorí pé ojúkójú ni ẹnikẹ́ni lè fi wo ilé tí kò ní olórí. Ní tiwa, olórí tó dára jù ni a ní. | Oludarii wa ni, ko si eni ti a le fi we e ninu egbee wa. Oun ni obii wa, oun ni o n gba wa nimoran. Idi niyi ti mo se ni ki gbogbo omo egbe pon on le nitori pe ojukoju ni enikeni le fi wo ile ti ko ni olori. Ni tiwa, olori to dara ju ni a ni. |
Bí àwọn CNN-FDD ṣe gbé oyè náà ní yẹpẹrẹ tó ipò agbára Nkurunziza gẹ́gẹ́ bí adarí ayérayé tó ga jù ti jẹ́ kí ó nira fún ẹnikẹ́ni láti kọ ohunkóhun tí ó bá yàn láti ṣe, títí mọ́ ìgbésẹ̀ rẹ̀ láti ṣe àyípadà òfin sáà méjì fún ipò adarí tí ó wà nínú ìwé òfin orílẹ̀-èdè náà. Èyí ń ṣe àfihàn àdálò tí ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà lórí oyè ń dá agbára lò pẹ̀lú Nkurunziza àti àwọn alátìlẹyìn-in rẹ̀ pẹ̀lú bí ẹgbẹ́ òṣèlú náà ṣe ń darí àwọn ìdásílẹ̀ ìjọba. | Bi awon CNN-FDD se gbe oye naa ni yepere to ipo agbara Nkurunziza gege bi adari ayeraye to ga ju ti je ki o nira fun enikeni lati ko ohunkohun ti o ba yan lati se, titi mo igbese re lati se ayipada ofin saa meji fun ipo adari ti o wa ninu iwe ofin orile-ede naa. Eyi n se afihan adalo ti egbe oselu to wa lori oye n da agbara lo pelu Nkurunziza ati awon alatileyin-in re pelu bi egbe oselu naa se n dari awon idasile ijoba. |
Àwọn oníkọkúkọ ní ìṣọ̀kan | Awon onikokuko ni isokan |
Àwọn ọmọ ìlú tí wọ́n ń ṣàmúlò ayélujára ti bẹ̀rẹ̀ ìkọkúkọ sórí àwòrán ààrẹ Nkurunziza nínú ìfẹ̀hónúhàn pẹ̀lú àmì ìdámọ̀: Nkurunziza àti Burundi: | Awon omo ilu ti won n samulo ayelujara ti bere ikokuko sori aworan aare Nkurunziza ninu ifehonuhan pelu ami idamo: Nkurunziza ati Burundi: |
Ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga ní ẹ̀wọ̀n fún kíkọ ìkọkúkọ sí orí àwòrán Ààrẹ . | Omo ile eko giga ni ewon fun kiko ikokuko si ori aworan Aare . |
Bí mo bá ṣe èyí ní Burundi , ó ṣe é ṣe kí a fi mí sí àtìmọ́lé | Bi mo ba se eyi ni Burundi , o se e se ki a fi mi si atimole |