diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
tí o (lọ) tààrà. Nítorí náà ẹ tẹ̀lé e;
ti o (lo) taara. Nitori naa e tele e;
Ó kó àwọn tabili òkúta mejeeji sinu àpótí ẹ̀rí náà, ó ti àwọn ọ̀pá àpótí náà bọ inú àwọn òrùka rẹ̀, ó sì fi ìdérí rẹ̀ dé e lórí. Ibinu OLUWA ru sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì mú wọn rìn kiri ninu aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún títí gbogbo àwọn tí wọ́n ṣe burúkú níwájú OLUWA fi kú tán. Kí Ọlọrun Olodumare jẹ́ kí ọkunrin náà ṣàánú yín, kí ó sì dá arakunrin yín kan yòókù ati Bẹnjamini pada. Bí mo bá tilẹ̀ wá ṣòfò àwọn ọmọ mi nígbà náà, n óo gbà pé mo ṣòfò wọn.”Wọ́n ṣe ọgbà náà lọ́ṣọ̀ọ́ pẹlu aṣọ aláwọ̀ aró ati aṣọ funfun. Wọ́n fi òwú funfun ati òwú àlàárì ṣe okùn, wọ́n fi so wọ́n mọ́ òrùka fadaka, wọ́n gbé wọn kọ́ sára òpó òkúta mabu. Wúrà ati fadaka ni wọ́n fi ṣe àwọn àga tí ó wà ninu ọgbà. Òkúta mabu pupa ati aláwọ̀ aró ni wọ́n fi ṣe gbogbo ọ̀dẹ̀dẹ̀, tí gbogbo wọn ń dán gbinringbinrin. Ohunkohun tí wọ́n bá sọ fun yín ní ibi tí OLUWA bá yàn ni ẹ gbọdọ̀ ṣe. Ẹ gbọdọ̀ ṣọ́ra, kí ẹ sì ṣe gbogbo ohun tí wọ́n bá ní kí ẹ ṣe. Kí àwọn ọmọ Israẹli má baà tún máa fi ẹran wọn rúbọ sí oriṣa bí wọ́n ti ń ṣe rí. Òfin yìí wà fún arọmọdọmọ wọn títí lae.Lẹ́yìn náà, àwọn baba ńlá yín kígbe pe OLUWA fún ìrànlọ́wọ́. Wọ́n ní, ‘A ti ṣẹ̀, nítorí pé a ti kọ OLUWA sílẹ̀, a sì ń sin oriṣa Baali, ati ti Aṣitarotu. Nisinsinyii, gbà wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa, a óo sì máa sìn ọ́.’ Ṣe é ní ẹlẹ́mìí kúkúrú,kí ohun ìní rẹ̀ di ti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà.Kí ẹ wá dáríjì í. Kí ẹ fún un ní ìwúrí. Bí ìbànújẹ́ bá tún pọ̀ lápọ̀jù kí ó má baà wó irú ẹni bẹ́ẹ̀ mọ́lẹ̀. “Ẹ̀rí ẹyọ ẹnìkan ṣoṣo péré kò tó láti fi dá ẹnikẹ́ni lẹ́bi lórí ẹ̀sùnkẹ́sùn tí wọ́n bá fi kàn án, tabi ẹ̀ṣẹ̀kẹ́ṣẹ̀ tí ó bá ṣẹ̀. Ẹlẹ́rìí gbọdọ̀ tó meji tabi mẹta, kí ẹ tó lè dá ẹnikẹ́ni lẹ́bi lórí ẹ̀sùn kan. 140. 'Ní ti àwọn wònyí, dájúdájú
O ko awon tabili okuta mejeeji sinu apoti eri naa, o ti awon opa apoti naa bo inu awon oruka re, o si fi ideri re de e lori. Ibinu OLUWA ru si awon omo Israeli, o si mu won rin kiri ninu asale fun ogoji odun titi gbogbo awon ti won se buruku niwaju OLUWA fi ku tan. Ki Olorun Olodumare je ki okunrin naa saanu yin, ki o si da arakunrin yin kan yooku ati Benjamini pada. Bi mo ba tile wa sofo awon omo mi nigba naa, n oo gba pe mo sofo won.”Won se ogba naa losoo pelu aso alawo aro ati aso funfun. Won fi owu funfun ati owu alaari se okun, won fi so won mo oruka fadaka, won gbe won ko sara opo okuta mabu. Wura ati fadaka ni won fi se awon aga ti o wa ninu ogba. Okuta mabu pupa ati alawo aro ni won fi se gbogbo odede, ti gbogbo won n dan gbinringbinrin. Ohunkohun ti won ba so fun yin ni ibi ti OLUWA ba yan ni e gbodo se. E gbodo sora, ki e si se gbogbo ohun ti won ba ni ki e se. Ki awon omo Israeli ma baa tun maa fi eran won rubo si orisa bi won ti n se ri. Ofin yii wa fun aromodomo won titi lae.Leyin naa, awon baba nla yin kigbe pe OLUWA fun iranlowo. Won ni, ‘A ti se, nitori pe a ti ko OLUWA sile, a si n sin orisa Baali, ati ti Asitarotu. Nisinsinyii, gba wa lowo awon ota wa, a oo si maa sin o.’ Se e ni elemii kukuru,ki ohun ini re di ti awon alonilowogba.Ki e wa dariji i. Ki e fun un ni iwuri. Bi ibanuje ba tun po lapoju ki o ma baa wo iru eni bee mole. “Eri eyo enikan soso pere ko to lati fi da enikeni lebi lori esunkesun ti won ba fi kan an, tabi esekese ti o ba se. Elerii gbodo to meji tabi meta, ki e to le da enikeni lebi lori esun kan. 140. 'Ni ti awon wonyi, dajudaju
gbogbo ohun tí wọn gbé dání ni
gbogbo ohun ti won gbe dani ni
yòò parun, asán sì ni gbogbo
yoo parun, asan si ni gbogbo
ohun tí wọn n ṣe níṣẹ yòò jásí."
ohun ti won n se nise yoo jasi."
141. Òun (Musa) wí pé: 'Emi
141. Oun (Musa) wi pe: 'Emi
yòò ha wá Ọlọrun mìíràn fún yín,
yoo ha wa Olorun miiran fun yin,
lẹhìn Allah, bí? Nígbà tí ô Jẹ pé
lehin Allah, bi? Nigba ti o Je pe
Òun lò dá yín lọlá ju gbogbo ẹ̀dá
Oun lo da yin lola ju gbogbo eda
yòòkù lọ?"
yooku lo?"
142. Kí ẹ sì rántí nígbà tí Àwa
142. Ki e si ranti nigba ti Awa
gbà yín là kúrò lỌwọ: àwọn
gba yin la kuro lOwo: awon
ẹ̀nìyàn Fir aona tí wQn n fi ìyá
eniyan Fir aona ti wQn n fi iya
búburú jẹ yín, tí wọn n pa àwọn
buburu je yin, ti won n pa awon
ọmọ yin lọkùnrin tí wọn sì n dá
omo yin lokunrin ti won si n da
àwọn obìnrin sí. Eyí sì j€ àdánwò
awon obinrin si. Eyi si j€ adanwo
nlá fún yín láti ọdò Olúwa yín.
nla fun yin lati odo Oluwa yin.
ÌDÁ 17
IDA 17
143. A sì bá Musa ṣe àdéhùn
143. A si ba Musa se adehun
ọgbọn òru, lẹhìn náà ni A tún fi
ogbon oru, lehin naa ni A tun fi
mẹwàá kún un. Nitorí náà àkòkò
mewaa kun un. Nitori naa akoko
ti Olúwa rẹ̀ yàn di ogéjì òru
ti Oluwa re yan di ogeji oru
géérégé.. Musa. sì. wí fún
geerege.. Musa. si. wi fun
arákùnrin rẹ̀, Aarun pé, 'Ròlé dẹ̀
arakunrin re, Aarun pe, 'Role de
mi laàrin àwọn ẹ̀nìyàn mi, kí o sì
mi laarin awon eniyan mi, ki o si
máa ṣe àtúnṣe, kí o má sì ṣe tẹ̀lé
maa se atunse, ki o ma si se tele
ònà àwọn
ona awon
144. Nígbà tí Musa dé ní àkòkò tí
144. Nigba ti Musa de ni akoko ti
a dá, Olúwa rẹ̀ sì bá a sọrọ, òun
a da, Oluwa re si ba a soro, oun
(Musa) wi pé: 'Olúwa mi, fi hàn
(Musa) wi pe: 'Oluwa mi, fi han
mí bí mo ti ṣe lẹ̀ rí Ọ." Òun sì wí
mi bi mo ti se le ri O." Oun si wi
pé, 'Ìwọ kò le rí Mi, ṣùgbọn wo
pe, 'Iwo ko le ri Mi, sugbon wo
ẹni tí ó fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, kí ó lè gbà wá kúrò lọ́wọ́ ayé wa burúkú yìí, gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọrun Baba wa, Àwọn nǹkan mẹfa kan wà tí OLUWA kò fẹ́:wọ́n tilẹ̀ tó meje tí ó jẹ́ ohun ìríra fún un:Lórí òkè gíga fíofío, ni o lọ tẹ́ ibùsùn rẹ síníbẹ̀ ni o tí ń lọ rú ẹbọ.Mọ̀ dájú pé bẹ́ẹ̀ ni ọgbọ́n yóo rí fún ọ,bí o bá ní i, yóo dára fún ọ lẹ́yìn ọ̀la,ìrètí rẹ kò sì ní di asán.Wọ́n bá lọ, wọ́n sì ṣe bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose ati Aaroni.Kí ló dé tí o fi kà wá sí ẹranko,tí a di òmùgọ̀ lójú rẹ?Àwọn nǹkan wọnyi ni wọ́n ń sọ eniyan di aláìmọ́; kí eniyan jẹun láì wẹ ọwọ́ kò lè sọ eniyan di aláìmọ́.”Àwọn ará Filistia fi oriṣa wọn sílẹ̀ nígbà tí wọn ń sá lọ, Dafidi sì pàṣẹ pé kí wọ́n sun wọ́n níná.Mikali, ọmọbinrin Saulu, kò sì bímọ títí ó fi kú.Angẹli náà sọ fún un pé, “Di ìgbànú rẹ, sì wọ sálúbàtà rẹ.” Peteru bá ṣe bí angẹli náà ti wí. Angẹli yìí tún sọ fún un pé, “Da aṣọ rẹ bora, kí o máa tẹ̀lé mi.” Miriamu bá dá orin fún wọn pé,“Ẹ kọrin sí OLUWA,nítorí tí ó ti ja àjàṣẹ́gun tí ó lógo,ó ti da ati ẹṣin ati àwọn ẹlẹ́ṣin sinu Òkun Pupa.”“Báwo ni ẹnìkan ṣe lè wọ ilé alágbára lọ, kí ó kó o lẹ́rù, bí kò bá kọ́kọ́ de alágbára náà? Bí ó bá kọ́kọ́ dè é ni yóo tó lè kó o lẹ́rù. Ṣugbọn ẹnu ya Pilatu pé Jesu ti yára kú! Ó pe ọ̀gágun, ó bèèrè bí Jesu ti kú tipẹ́. For the exceptionally brave person the proper profession is warring; for the gregarious person, trading; the illustrious he-goat, even when it is poor, finds enough to eat.
eni ti o fi emi re lele nitori ese wa, ki o le gba wa kuro lowo aye wa buruku yii, gege bi ife Olorun Baba wa, Awon nnkan mefa kan wa ti OLUWA ko fe:won tile to meje ti o je ohun irira fun un:Lori oke giga fiofio, ni o lo te ibusun re sinibe ni o ti n lo ru ebo.Mo daju pe bee ni ogbon yoo ri fun o,bi o ba ni i, yoo dara fun o leyin ola,ireti re ko si ni di asan.Won ba lo, won si se bi OLUWA ti pase fun Mose ati Aaroni.Ki lo de ti o fi ka wa si eranko,ti a di omugo loju re?Awon nnkan wonyi ni won n so eniyan di alaimo; ki eniyan jeun lai we owo ko le so eniyan di alaimo.”Awon ara Filistia fi orisa won sile nigba ti won n sa lo, Dafidi si pase pe ki won sun won nina.Mikali, omobinrin Saulu, ko si bimo titi o fi ku.Angeli naa so fun un pe, “Di igbanu re, si wo salubata re.” Peteru ba se bi angeli naa ti wi. Angeli yii tun so fun un pe, “Da aso re bora, ki o maa tele mi.” Miriamu ba da orin fun won pe,“E korin si OLUWA,nitori ti o ti ja ajasegun ti o logo,o ti da ati esin ati awon elesin sinu Okun Pupa.”“Bawo ni enikan se le wo ile alagbara lo, ki o ko o leru, bi ko ba koko de alagbara naa? Bi o ba koko de e ni yoo to le ko o leru. Sugbon enu ya Pilatu pe Jesu ti yara ku! O pe ogagun, o beere bi Jesu ti ku tipe. For the exceptionally brave person the proper profession is warring; for the gregarious person, trading; the illustrious he-goat, even when it is poor, finds enough to eat.
Hagari bí ọmọkunrin kan fún Abramu, Abramu sì sọ ọmọ náà ní Iṣimaeli. Ní gbogbo àkókò yìí, Josẹfu ni gomina ilẹ̀ Ijipti, òun ni ó ń ta ọkà fún àwọn eniyan láti gbogbo orílẹ̀-èdè. Nígbà tí àwọn arakunrin rẹ̀ dé, wọ́n kí i, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀. Orúkọ wọn ni: Otini, Refaeli, Obedi, ati Elisabadi, ati àwọn arakunrin wọn, Elihu ati Semakaya, tí wọ́n jẹ́ alágbára eniyan.Òun óo mú Jehoiakini ọba Juda, ọmọ Jehoiakimu, ati gbogbo àwọn tí a kó lẹ́rú láti Juda lọ sí Babiloni pada sí ibí yìí, nítorí òun óo ṣẹ́ àjàgà ọba Babiloni. Ó ní OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.” Samuẹli bá bá a pada, Saulu sì sin OLUWA níbẹ̀.Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ bá ń bá tiwọn lọ, Ṣimei sì ń tẹ̀lé wọn lẹ́gbẹ̀ẹ́ keji òkè náà, bí ó ti ń tẹ̀lé wọn, bẹ́ẹ̀ ni ó ń ṣépè, ó ń sọ òkúta lù ú, ó sì ń da erùpẹ̀ sí wọn lára. Ìyọnu ati ìpayà dé bá mi,ṣugbọn mo láyọ̀ ninu òfin rẹ.Nígbà tí wọ́n pinnu láti fi wá ranṣẹ sí Itali, wọ́n fi Paulu ati àwọn ẹlẹ́wọ̀n mìíràn lé balogun ọ̀rún kan tí ó ń jẹ́ Juliọsi lọ́wọ́, ó jẹ́ ọ̀gágun ti ẹgbẹ́ kan tí wọn ń pè ní Ọmọ-ogun Augustu. Bí apànìyàn kan bá sá lọ sí ìlú ààbò, ẹ kò gbọdọ̀ gba owó ìtanràn lọ́wọ́ rẹ̀, kí ó baà lè pada sí ilẹ̀ ìní rẹ̀ ṣáájú ikú olórí alufaa. O sọ fún àwa iranṣẹ rẹ pé kí á mú un tọ̀ ọ́ wá, kí o lè fi ojú rí i. Nígbà náà ni wolii Aisaya lọ sí ọ̀dọ̀ Hesekaya, ó bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Níbo ni àwọn ọkunrin wọnyi ti wá, kí ni wọ́n sì sọ fún ọ?”Hesekaya dáhùn pé, “Ọ̀nà jíjìn ni wọ́n ti wá, láti Babiloni.”Solomoni ọba ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli péjọ níwájú Àpótí Ẹ̀rí OLUWA, wọ́n sì fi ọpọlọpọ aguntan ati mààlúù tí ẹnikẹ́ni kò lè kà rúbọ. Àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi ati àwọn ọ̀tá mi pọ̀,ṣugbọn n kò yapa kúrò ninu ìlànà rẹ.Oòrùn, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀ yóo gbọ̀n dànùa óo ká awọsanma bí ẹni ká ìwé.Oòrùn, òṣùpá, ati àwọn ìràwọ̀ yóo jábọ́bí ewé tií rẹ̀ sílẹ̀ lára ìtàkùn àjàrà,àní, bí ewé tií wọ́ dànù lórí igi ọ̀pọ̀tọ́.wọ́n wọ ọkọ̀, wọ́n ń lọ sí Kapanaumu ní òdìkejì òkun. Òkùnkùn ti ṣú ṣugbọn Jesu kò ì tíì dé ọ̀dọ̀ wọn. mo sì fún Baruku ọmọ Neraya ọmọ Mahiseaya ní èyí tí a fi òǹtẹ̀ tẹ̀, níṣojú Hanameli, ọmọ arakunrin baba mi ati níṣojú àwọn ẹlẹ́rìí tí wọn fọwọ́ sí ìwé ilẹ̀ náà, ati níṣojú gbogbo àwọn ará Juda tí wọn jókòó ní àgbàlá àwọn olùṣọ́ náà. Ó sọ fún un nígbà náà pé, “Gba àwọn ohun èèlò wọnyi, kó wọn lọ sinu tẹmpili tí ó wà ní Jerusalẹmu, kí ẹ sì tún tẹmpili náà kọ́ sí ojú ibi tí ó wà tẹ́lẹ̀.” Gbogbo eniyan ni wọ́n ń ròyìn Demeteriu ní rere. Òtítọ́ pàápàá ń jẹ́rìí rẹ̀. Èmi náà jẹ́rìí sí i, o sì mọ̀ pé òtítọ́ ni ẹ̀rí mi.Ṣugbọn bí apànìyàn náà bá rékọjá odi ìlú ààbò rẹ̀, Gbogbo ìlú tí wọ́n fún àwọn ọmọ Lefi ninu ilẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli jẹ́ mejidinlaadọta pẹlu àwọn pápá ìdaran tí ó wà ní àyíká wọn. Ẹ wí láàrin àwọn orílẹ̀-èdè pé, “OLUWA jọba!A ti fi ìdí ayé múlẹ̀, kò sì ní yẹ̀ lae;OLUWA yóo fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan.”Ṣugbọn Oluwa dá a lóhùn pé, “Mata! Mata! Ò ń ṣe aájò, o sì ń dààmú nípa ohun pupọ. Báyìí ni ojú àwọn mẹrẹẹrin ati ìyẹ́ wọn rí: Ìyẹ́ wọn ń kan ara wọn; bí wọ́n bá ń rìn, olukuluku wọn á máa lọ siwaju tààrà, láìyà sí ibikíbi, bí wọn tí ń lọ. Ṣugbọn ọkàn wọn ti le, nítorí títí di ọjọ́ òní, aṣọ náà ni ó ń bo ọkàn wọn nígbà tí wọn bá ń ka ìwé majẹmu àtijọ́. Wọn kò mú aṣọ náà kúrò, nítorí nípasẹ̀ Kristi ni majẹmu àtijọ́ fi di asán. A person who waits patiently for a long time before eating will not eat unwholesome food.
Hagari bi omokunrin kan fun Abramu, Abramu si so omo naa ni Isimaeli. Ni gbogbo akoko yii, Josefu ni gomina ile Ijipti, oun ni o n ta oka fun awon eniyan lati gbogbo orile-ede. Nigba ti awon arakunrin re de, won ki i, won wole niwaju re. Oruko won ni: Otini, Refaeli, Obedi, ati Elisabadi, ati awon arakunrin won, Elihu ati Semakaya, ti won je alagbara eniyan.Oun oo mu Jehoiakini oba Juda, omo Jehoiakimu, ati gbogbo awon ti a ko leru lati Juda lo si Babiloni pada si ibi yii, nitori oun oo se ajaga oba Babiloni. O ni OLUWA lo so bee.” Samueli ba ba a pada, Saulu si sin OLUWA nibe.Dafidi ati awon eniyan re ba n ba tiwon lo, Simei si n tele won legbee keji oke naa, bi o ti n tele won, bee ni o n sepe, o n so okuta lu u, o si n da erupe si won lara. Iyonu ati ipaya de ba mi,sugbon mo layo ninu ofin re.Nigba ti won pinnu lati fi wa ranse si Itali, won fi Paulu ati awon elewon miiran le balogun orun kan ti o n je Juliosi lowo, o je ogagun ti egbe kan ti won n pe ni Omo-ogun Augustu. Bi apaniyan kan ba sa lo si ilu aabo, e ko gbodo gba owo itanran lowo re, ki o baa le pada si ile ini re saaju iku olori alufaa. O so fun awa iranse re pe ki a mu un to o wa, ki o le fi oju ri i. Nigba naa ni wolii Aisaya lo si odo Hesekaya, o beere lowo re pe, “Nibo ni awon okunrin wonyi ti wa, ki ni won si so fun o?”Hesekaya dahun pe, “Ona jijin ni won ti wa, lati Babiloni.”Solomoni oba ati gbogbo awon omo Israeli pejo niwaju Apoti Eri OLUWA, won si fi opolopo aguntan ati maaluu ti enikeni ko le ka rubo. Awon ti n se inunibini mi ati awon ota mi po,sugbon n ko yapa kuro ninu ilana re.Oorun, osupa, ati awon irawo yoo gbon danua oo ka awosanma bi eni ka iwe.Oorun, osupa, ati awon irawo yoo jabobi ewe tii re sile lara itakun ajara,ani, bi ewe tii wo danu lori igi opoto.won wo oko, won n lo si Kapanaumu ni odikeji okun. Okunkun ti su sugbon Jesu ko i tii de odo won. mo si fun Baruku omo Neraya omo Mahiseaya ni eyi ti a fi onte te, nisoju Hanameli, omo arakunrin baba mi ati nisoju awon elerii ti won fowo si iwe ile naa, ati nisoju gbogbo awon ara Juda ti won jokoo ni agbala awon oluso naa. O so fun un nigba naa pe, “Gba awon ohun eelo wonyi, ko won lo sinu tempili ti o wa ni Jerusalemu, ki e si tun tempili naa ko si oju ibi ti o wa tele.” Gbogbo eniyan ni won n royin Demeteriu ni rere. Otito paapaa n jerii re. Emi naa jerii si i, o si mo pe otito ni eri mi.Sugbon bi apaniyan naa ba rekoja odi ilu aabo re, Gbogbo ilu ti won fun awon omo Lefi ninu ile awon omo Israeli je mejidinlaadota pelu awon papa idaran ti o wa ni ayika won. E wi laarin awon orile-ede pe, “OLUWA joba!A ti fi idi aye mule, ko si ni ye lae;OLUWA yoo fi otito se idajo awon eniyan.”Sugbon Oluwa da a lohun pe, “Mata! Mata! O n se aajo, o si n daamu nipa ohun pupo. Bayii ni oju awon mereerin ati iye won ri: Iye won n kan ara won; bi won ba n rin, olukuluku won a maa lo siwaju taara, laiya si ibikibi, bi won ti n lo. Sugbon okan won ti le, nitori titi di ojo oni, aso naa ni o n bo okan won nigba ti won ba n ka iwe majemu atijo. Won ko mu aso naa kuro, nitori nipase Kristi ni majemu atijo fi di asan. A person who waits patiently for a long time before eating will not eat unwholesome food.
Ṣugbọn ó ranti ìgbà àtijọ́,ní àkókò Mose, iranṣẹ rẹ̀.Wọ́n bèèrè pé,ẹni tí ó kó wọn la òkun já dà?Olùṣọ́-aguntan agbo rẹ̀,tí ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ sáàrin wọn?Aláǹgbá tó já látorí ìrókò tí kò fẹsẹ̀ ṣẹ́, ó ní bẹ́nìkan ò yìn un òun ó yinra òun.
Sugbon o ranti igba atijo,ni akoko Mose, iranse re.Won beere pe,eni ti o ko won la okun ja da?Oluso-aguntan agbo re,ti o fi Emi Mimo re saarin won?Alangba to ja latori iroko ti ko fese se, o ni benikan o yin un oun o yinra oun.
Nítorí náà, mo bẹ̀ ọ́, dáríjì mí, kí o sì bá mi pada, kí n lọ sin OLUWA níbẹ̀.”Ìdí nìyí tí ẹ̀rù fi bà mí níwájú rẹ̀,tí mo bá ro nǹkan wọnyi, jìnnìjìnnì rẹ̀ a bò mí.Àtẹ ìfẹ́kà ń bẹ lọ́wọ́ rẹ̀ tí yóo fi fẹ́ ọkà inú oko rẹ̀; yóo kó ọkà rẹ̀ sinu abà, yóo sì sun fùlùfúlù ninu iná àjóòkú.”Nígbà tí àwọn afọnfèrè bá fọn fèrè mejeeji, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli yóo wá sọ́dọ̀ rẹ ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ. Ìrísí wọn bani lẹ́rù; wọ́n ń fi ọlá ńlá wọn ṣe ìdájọ́ bí ó ti wù wọ́n.Nítorí pé wọn kì í tètè dá ẹjọ́ àwọn ẹni ibi, ni ọkàn ọmọ eniyan fi kún fún ìwà ibi. Ó ṣe! Ọjọ́ náà ń bọ̀,ọjọ́ OLUWA dé tán!Ọjọ́ náà yóo dé bí ọjọ́ ìparun láti ọ̀dọ̀ Olodumare. Jesu bá sọ fún àwọn eniyan ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, Jesu bi wọ́n pé, “Burẹdi mélòó ni ẹ ní?”Wọ́n ní, “Meje, ati ẹja kéékèèké díẹ̀.”Abrahamu jẹ́ ẹni ọgọrun-un (100) ọdún nígbà tí a bí Isaaki fún un. Nígbà tí àwọn ọmọ àwọn wolii tí wọ́n wà ní Jẹriko rí i, wọ́n ní, “Ẹ̀mí Elija ti wà lára Eliṣa!” Wọ́n lọ pàdé rẹ̀, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀, Àwọn iranṣẹ Huramu ati àwọn iranṣẹ Solomoni tí wọ́n mú wúrà wá láti Ofiri, tún mú igi aligumu ati àwọn òkúta olówó iyebíye wá pẹlu. Ṣugbọn Jesu mọ ohun tí wọn ń sọ, ó ní, “Kí ló dé tí ẹ fi ń sọ láàrin ara yín nípa oúnjẹ tí ẹ kò ní, ẹ̀yin onigbagbọ kékeré? Nígbà náà ni àwọn eniyan náà gbéra ninu àgọ́ wọn láti la odò Jọdani kọjá pẹlu àwọn alufaa tí wọn ń gbé Àpótí Majẹmu lọ níwájú wọn, Mo gbọ́ pé ò ń gé irun àwọn aguntan rẹ, mo sì fẹ́ kí o mọ̀ pé àwọn olùṣọ́ aguntan rẹ wà lọ́dọ̀ wa fún ìgbà pípẹ́, n kò sì ṣe wọ́n ní ibi kankan. Kò sí ohun tí ó jẹ́ tiwọn tí ó sọnù ní gbogbo ìgbà tí wọ́n wà ní Kamẹli. Wọ́n dá a lóhùn, wọ́n ní, “Baba wa, iranṣẹ rẹ ń bẹ láàyè, ó sì wà ní alaafia.” Wọ́n tẹríba, wọ́n bu ọlá fún un. Ṣugbọn kí ni mo lè sọ?Nítorí pé ó ti bá mi sọ̀rọ̀,òun fúnrarẹ̀ ni ó sì ṣe éOorun kò kùn mí nítorí pé ọkàn mi bàjẹ́.Saulu wí fún Samuẹli pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, mo ti dẹ́ṣẹ̀. Mo ti ṣe àìgbọràn sí òfin OLUWA ati sí ọ̀rọ̀ rẹ̀ nítorí pé mo bẹ̀rù àwọn eniyan mi, mo sì ṣe ohun tí wọ́n fẹ́. Alákatam̀pò ojú ò lè ta ẹran pa.
Nitori naa, mo be o, dariji mi, ki o si ba mi pada, ki n lo sin OLUWA nibe.”Idi niyi ti eru fi ba mi niwaju re,ti mo ba ro nnkan wonyi, jinnijinni re a bo mi.Ate ifeka n be lowo re ti yoo fi fe oka inu oko re; yoo ko oka re sinu aba, yoo si sun fulufulu ninu ina ajooku.”Nigba ti awon afonfere ba fon fere mejeeji, gbogbo awon omo Israeli yoo wa sodo re ni enu ona Ago Ajo. Irisi won bani leru; won n fi ola nla won se idajo bi o ti wu won.Nitori pe won ki i tete da ejo awon eni ibi, ni okan omo eniyan fi kun fun iwa ibi. O se! Ojo naa n bo,ojo OLUWA de tan!Ojo naa yoo de bi ojo iparun lati odo Olodumare. Jesu ba so fun awon eniyan ati awon omo-eyin re pe, Jesu bi won pe, “Buredi meloo ni e ni?”Won ni, “Meje, ati eja keekeeke die.”Abrahamu je eni ogorun-un (100) odun nigba ti a bi Isaaki fun un. Nigba ti awon omo awon wolii ti won wa ni Jeriko ri i, won ni, “Emi Elija ti wa lara Elisa!” Won lo pade re, won wole niwaju re, Awon iranse Huramu ati awon iranse Solomoni ti won mu wura wa lati Ofiri, tun mu igi aligumu ati awon okuta olowo iyebiye wa pelu. Sugbon Jesu mo ohun ti won n so, o ni, “Ki lo de ti e fi n so laarin ara yin nipa ounje ti e ko ni, eyin onigbagbo kekere? Nigba naa ni awon eniyan naa gbera ninu ago won lati la odo Jodani koja pelu awon alufaa ti won n gbe Apoti Majemu lo niwaju won, Mo gbo pe o n ge irun awon aguntan re, mo si fe ki o mo pe awon oluso aguntan re wa lodo wa fun igba pipe, n ko si se won ni ibi kankan. Ko si ohun ti o je tiwon ti o sonu ni gbogbo igba ti won wa ni Kameli. Won da a lohun, won ni, “Baba wa, iranse re n be laaye, o si wa ni alaafia.” Won teriba, won bu ola fun un. Sugbon ki ni mo le so?Nitori pe o ti ba mi soro,oun funrare ni o si se eOorun ko kun mi nitori pe okan mi baje.Saulu wi fun Samueli pe, “Bee ni, mo ti dese. Mo ti se aigboran si ofin OLUWA ati si oro re nitori pe mo beru awon eniyan mi, mo si se ohun ti won fe. Alakatampo oju o le ta eran pa.
Ṣugbọn wọ́n hùwà ọlọ̀tẹ̀:wọ́n sì mú Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ bínú.Nítorí náà ó di ọ̀tá wọn,ó sì dojú ìjà kọ wọ́n.It is a bald person that may be disdainful of the razor.
Sugbon won huwa olote:won si mu Emi Mimo re binu.Nitori naa o di ota won,o si doju ija ko won.It is a bald person that may be disdainful of the razor.
The bald person has no use for razors. Compare Àpáàdì ló tó ko iná lójú.
The bald person has no use for razors. Compare Apaadi lo to ko ina loju.
Ṣugbọn títí di ọjọ́ òní, nígbàkúùgbà tí wọn bá ń ka Òfin Mose, aṣọ a máa bo ọkàn wọn. Wọ́n ní ọwọ́ eniyan lábẹ́ ìyẹ́ wọn mẹrẹẹrin, wọ́n ní ojú mẹ́rin ati ìyẹ́ mẹ́rin. Ṣugbọn Mata kò rójú nítorí aájò tí ó ń ṣe nípa oúnjẹ. Ni Mata bá wá, ó ní, “Alàgbà, arabinrin mi fi èmi nìkan sílẹ̀ láti máa tọ́jú oúnjẹ, o sì dákẹ́ ò ń wò ó níran! Sọ fún un kí ó wá ràn mí lọ́wọ́.”Jẹ́ kí inú ọ̀run ó dùn, sì jẹ́ kí ayé ó yọ̀;kí òkun ó hó, ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀.Ìlú mejila ni wọ́n fún àwọn ìdílé yòókù ninu ẹ̀yà Lefi tí à ń pè ní Merari gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.tí arakunrin ẹni tí ó pa bá rí i tí ó sì pa á, olùgbẹ̀san náà kì yóo ní ẹ̀bi; Mo ní ohun pupọ tí mo fẹ́ bá ọ sọ, ṣugbọn n kò fẹ́ kọ ọ́ sinu ìwé. Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí èbúté, Ó dá àwọn ohun èlò wúrà ati ti fadaka pada, tí Nebukadinesari kó ninu ilé OLUWA ní Jerusalẹmu, lọ sí ilé oriṣa rẹ̀ ní Babiloni tẹ́lẹ̀. Gbogbo nǹkan wọnyi ni Kirusi ọba kó jáde kúrò ninu tẹmpili ní Babiloni, ó kó wọn lé Ṣeṣibasari lọ́wọ́, ẹni tí ó yàn ní gomina lórí Juda. Mo pàṣẹ fún Baruku níṣojú wọn pé, Nítorí mo ti rẹkẹ idà mi lókè ọ̀run,yóo sọ̀kalẹ̀ láti ṣe ìdájọ́ àwọn ará Edomu;yóo sọ̀kalẹ̀ sórí àwọn tí mo fẹ́ parun.Àánú rẹ pọ̀, OLUWA,sọ mí di alààyè gẹ́gẹ́ bí òtítọ́ rẹ.Àwọn ọmọ Lefi ati àwọn alufaa gbé Àpótí OLUWA wá, ati Àgọ́ OLUWA, ati àwọn ohun èlò mímọ́ tí ó wà ninu rẹ̀. Aisaya bá tún bèèrè pé, “Kí ni wọ́n rí ninu ààfin rẹ?”Ọba dáhùn, ó ní, “Kò sí ohun kan ninu ilé ìṣúra tí n kò fi hàn wọ́n.”A sì dá oluwa mi lóhùn pé, ‘A ní baba, ó ti di arúgbó, a sì ní arakunrin kan pẹlu, tí baba yìí fi arúgbó ara bí, ati pé ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ti kú, òun nìkan ṣoṣo ni ó kù lọ́mọ ìyá tirẹ̀, baba rẹ̀ sì fẹ́ràn rẹ̀.’ Ojú tí ó gbé sókè, ó rí Bẹnjamini ọmọ ìyá rẹ̀, ó bá bèèrè pé, “Ṣé arakunrin yín tí í ṣe àbíkẹ́yìn tí ẹ wí nìyí? Kí Ọlọrun fi ojurere wò ọ́, ọmọ mi.” Ọkàn mi ń ṣe hílàhílo bí ẹyẹ aláàpáǹdẹ̀dẹ̀ ati ẹyẹ àkọ̀,mò ń ké igbe arò bí àdàbà.Mo wòkè títí ojú ń ro mí,ara ń ní mí, OLUWA, nítorí náà ṣe ààbò mi.(àkókò náà jẹ́ àkókò ìkórè, odò Jọdani sì kún dé ẹnu), ṣugbọn bí àwọn alufaa tí wọ́n gbé Àpótí Majẹmu ti dé etídò náà, tí wọ́n sì fi ẹsẹ̀ wọn kan omi, Ó ní kí wọ́n kí i báyìí pé, “Alaafia fún ọ, ati fún ilé rẹ ati fún gbogbo ohun tí o ní. Òye kò ì tíì ye yín sibẹ? Ẹ kò ranti burẹdi marun-un tí mo fi bọ́ ẹgbẹẹdọgbọn (5,000) eniyan ati iye agbọ̀n àjẹkù tí ẹ kó jọ? Igi aligumu yìí ni ọba fi ṣe àtẹ̀gùn láti máa gòkè ati láti máa sọ̀kalẹ̀ ninu tẹmpili OLUWA ati ninu ààfin ọba. Ó tún fi ṣe dùùrù ati hapu fún àwọn akọrin. Kò sí irú wọn rí ní gbogbo ilẹ̀ Juda.Ó kọlà abẹ́ fún ọmọ náà nígbà tí ó di ọmọ ọjọ́ kẹjọ gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti pàṣẹ fún un. Jesu pàṣẹ kí àwọn eniyan jókòó nílẹ̀. Ó fi aṣọ àwọ̀lékè tí ó já bọ́ sílẹ̀ lára Elija lu odò, ó sì kígbe pé, “Níbo ni OLUWA Ọlọrun Elija wà?” Lẹ́yìn náà odò pín sí meji, Eliṣa bá kọjá sí òdìkejì. “Fi fadaka tí wọ́n fi òòlù lù ṣe fèrè meji fún pípe àwọn ọmọ Israẹli jọ ati títú ibùdó palẹ̀. Ẹ kéde ààwẹ̀, kí ẹ sì pe àpèjọ.Ẹ pe àwọn àgbààgbà, ati gbogbo àwọn tí ń gbé ilẹ̀ náà jọ sí ilé OLUWA Ọlọrun yín,kí ẹ sì kígbe pe OLUWA.Mo rí àwọn ẹni ibi tí a sin sí ibojì. Nígbà ayé wọn, wọn a ti máa ṣe wọlé-wọ̀de ní ibi mímọ́, àwọn eniyan a sì máa yìn wọ́n, ní ìlú tí wọn tí ń ṣe ibi. Asán ni èyí pẹlu.Wò ó! N óo gbé àwọn ará Kalidea dìde, orílẹ̀-èdè tí ó yára, tí kò sì ní àánú; àwọn tí wọ́n la ìbú ayé já, tí wọn ń gba ilẹ̀ onílẹ̀ káàkiri. Johanu sọ fún gbogbo eniyan pé, “Omi ni èmi fi ń ṣe ìwẹ̀mọ́ fun yín, ṣugbọn ẹni tí ó jù mí lọ ń bọ̀. Èmi kò tó ẹni tíí tú okùn bàtà rẹ̀. Ẹ̀mí Mímọ́ ati iná ni yóo fi wẹ̀ yín mọ́. Yóo ṣe ohun tí ó ti pinnu láti ṣe fún mi ní àṣeyọrí,ati ọpọlọpọ nǹkan bẹ́ẹ̀ yòókùtí ó tún ní lọ́kàn láti ṣe fún mi.“Ìgbàwo ni o óo sinmi ẹjọ́ tí ò ń tò yìí?Ohun tí a tí ń bá ọ sọ ni kí o gbé yẹ̀wò,kí á lè sọ èyí tí a tún fẹ́ sọ.Jesu jáde kúrò níbẹ̀, ó lọ sí agbègbè Tire ati Sidoni. Nígbà tí ó di ọ̀gànjọ́ òru, OLUWA lu gbogbo àwọn àkọ́bí ilẹ̀ Ijipti pa, ó bẹ̀rẹ̀ láti orí àrẹ̀mọ ọba Farao tí ó wà lórí ìtẹ́, títí kan àkọ́bí ẹrú tí ó wà ninu ọgbà ẹ̀wọ̀n, ati àkọ́bí gbogbo ẹran ọ̀sìn. Má lúgọ bí eniyan burúkú láti kó ilé olódodo,má fọ́ ilé rẹ̀.ẹni tí ògo yẹ fún lae ati laelae. Amin.Àwọn oriṣa láàrin àwọn òkúta ọ̀bọ̀rọ́, ninu àfonífojì,àwọn ni ẹ̀ ń sìn,àwọn ni ò ń da ẹbọ ohun mímu lé lórí,àwọn ni ò ń fi nǹkan jíjẹ rúbọ sí.Ṣé àwọn nǹkan wọnyi ni yóo mú kí inú mi yọ́?Ìgbéraga, irọ́ pípa,ẹni tí ń déédé pa aláìṣẹ̀,Àwọn olórí ìdílé àwọn ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri ati ẹ̀yà Manase ọmọ Josẹfu, wá sọ́dọ̀ Mose ati àwọn olórí ẹ̀yà Israẹli, 135. Nígbà tí ìyà náà sọ kalẹ̀ lé
Sugbon titi di ojo oni, nigbakuugba ti won ba n ka Ofin Mose, aso a maa bo okan won. Won ni owo eniyan labe iye won mereerin, won ni oju merin ati iye merin. Sugbon Mata ko roju nitori aajo ti o n se nipa ounje. Ni Mata ba wa, o ni, “Alagba, arabinrin mi fi emi nikan sile lati maa toju ounje, o si dake o n wo o niran! So fun un ki o wa ran mi lowo.”Je ki inu orun o dun, si je ki aye o yo;ki okun o ho, ati gbogbo ohun ti o wa ninu re.Ilu mejila ni won fun awon idile yooku ninu eya Lefi ti a n pe ni Merari gege bi iye idile won.ti arakunrin eni ti o pa ba ri i ti o si pa a, olugbesan naa ki yoo ni ebi; Mo ni ohun pupo ti mo fe ba o so, sugbon n ko fe ko o sinu iwe. Nigba ti ile su, awon omo-eyin re sokale lo si ebute, O da awon ohun elo wura ati ti fadaka pada, ti Nebukadinesari ko ninu ile OLUWA ni Jerusalemu, lo si ile orisa re ni Babiloni tele. Gbogbo nnkan wonyi ni Kirusi oba ko jade kuro ninu tempili ni Babiloni, o ko won le Sesibasari lowo, eni ti o yan ni gomina lori Juda. Mo pase fun Baruku nisoju won pe, Nitori mo ti reke ida mi loke orun,yoo sokale lati se idajo awon ara Edomu;yoo sokale sori awon ti mo fe parun.Aanu re po, OLUWA,so mi di alaaye gege bi otito re.Awon omo Lefi ati awon alufaa gbe Apoti OLUWA wa, ati Ago OLUWA, ati awon ohun elo mimo ti o wa ninu re. Aisaya ba tun beere pe, “Ki ni won ri ninu aafin re?”Oba dahun, o ni, “Ko si ohun kan ninu ile isura ti n ko fi han won.”A si da oluwa mi lohun pe, ‘A ni baba, o ti di arugbo, a si ni arakunrin kan pelu, ti baba yii fi arugbo ara bi, ati pe egbon re ti ku, oun nikan soso ni o ku lomo iya tire, baba re si feran re.’ Oju ti o gbe soke, o ri Benjamini omo iya re, o ba beere pe, “Se arakunrin yin ti i se abikeyin ti e wi niyi? Ki Olorun fi ojurere wo o, omo mi.” Okan mi n se hilahilo bi eye alaapandede ati eye ako,mo n ke igbe aro bi adaba.Mo woke titi oju n ro mi,ara n ni mi, OLUWA, nitori naa se aabo mi.(akoko naa je akoko ikore, odo Jodani si kun de enu), sugbon bi awon alufaa ti won gbe Apoti Majemu ti de etido naa, ti won si fi ese won kan omi, O ni ki won ki i bayii pe, “Alaafia fun o, ati fun ile re ati fun gbogbo ohun ti o ni. Oye ko i tii ye yin sibe? E ko ranti buredi marun-un ti mo fi bo egbeedogbon (5,000) eniyan ati iye agbon ajeku ti e ko jo? Igi aligumu yii ni oba fi se ategun lati maa goke ati lati maa sokale ninu tempili OLUWA ati ninu aafin oba. O tun fi se duuru ati hapu fun awon akorin. Ko si iru won ri ni gbogbo ile Juda.O kola abe fun omo naa nigba ti o di omo ojo kejo gege bi Olorun ti pase fun un. Jesu pase ki awon eniyan jokoo nile. O fi aso awoleke ti o ja bo sile lara Elija lu odo, o si kigbe pe, “Nibo ni OLUWA Olorun Elija wa?” Leyin naa odo pin si meji, Elisa ba koja si odikeji. “Fi fadaka ti won fi oolu lu se fere meji fun pipe awon omo Israeli jo ati titu ibudo pale. E kede aawe, ki e si pe apejo.E pe awon agbaagba, ati gbogbo awon ti n gbe ile naa jo si ile OLUWA Olorun yin,ki e si kigbe pe OLUWA.Mo ri awon eni ibi ti a sin si iboji. Nigba aye won, won a ti maa se wole-wode ni ibi mimo, awon eniyan a si maa yin won, ni ilu ti won ti n se ibi. Asan ni eyi pelu.Wo o! N oo gbe awon ara Kalidea dide, orile-ede ti o yara, ti ko si ni aanu; awon ti won la ibu aye ja, ti won n gba ile onile kaakiri. Johanu so fun gbogbo eniyan pe, “Omi ni emi fi n se iwemo fun yin, sugbon eni ti o ju mi lo n bo. Emi ko to eni tii tu okun bata re. Emi Mimo ati ina ni yoo fi we yin mo. Yoo se ohun ti o ti pinnu lati se fun mi ni aseyori,ati opolopo nnkan bee yookuti o tun ni lokan lati se fun mi.“Igbawo ni o oo sinmi ejo ti o n to yii?Ohun ti a ti n ba o so ni ki o gbe yewo,ki a le so eyi ti a tun fe so.Jesu jade kuro nibe, o lo si agbegbe Tire ati Sidoni. Nigba ti o di oganjo oru, OLUWA lu gbogbo awon akobi ile Ijipti pa, o bere lati ori aremo oba Farao ti o wa lori ite, titi kan akobi eru ti o wa ninu ogba ewon, ati akobi gbogbo eran osin. Ma lugo bi eniyan buruku lati ko ile olododo,ma fo ile re.eni ti ogo ye fun lae ati laelae. Amin.Awon orisa laarin awon okuta oboro, ninu afonifoji,awon ni e n sin,awon ni o n da ebo ohun mimu le lori,awon ni o n fi nnkan jije rubo si.Se awon nnkan wonyi ni yoo mu ki inu mi yo?Igberaga, iro pipa,eni ti n deede pa alaise,Awon olori idile awon omo Gileadi, omo Makiri ati eya Manase omo Josefu, wa sodo Mose ati awon olori eya Israeli, 135. Nigba ti iya naa so kale le
wọn lòrí, wọn wí pé: "Ìwọ Musa,
won lori, won wi pe: "Iwo Musa,
bá wa pe Olúwa rẹ loòrí àdéhùn tí
ba wa pe Oluwa re loori adehun ti
Ò ti bá ẹ ṣe. Bí ìwọ bá le mú
O ti ba e se. Bi iwo ba le mu
àjàkálẹ̀ àrùn náà kúrò fún wa,
ajakale arun naa kuro fun wa,
dájúdájú àwa yòò gbà ọ gbọ, a ô
dajudaju awa yoo gba o gbo, a o
sì jẹ kí àwọn ọmọ Israẹli máa ba
si je ki awon omo Israeli maa ba
ọ lọ.
o lo.
136. Nígbà tí A sì mú àjàkálẹ̀
136. Nigba ti A si mu ajakale
àrùn náà kúrò fún wọn, fún ìgbà
arun naa kuro fun won, fun igba
diẹ̀ tí A fi wọn sílẹ̀ lẹhìn náà ni
die ti A fi won sile lehin naa ni
wọn tún yẹ àdéhùn.
won tun ye adehun.
137. Nítorí náà Àwa gbẹ̀san lára
137. Nitori naa Awa gbesan lara
wọn, A sì tẹ̀ wQn rì sínú òkun,
won, A si te wQn ri sinu okun,
nítorí pé wọn pe àwọn Àmì Wa
nitori pe won pe awon Ami Wa
nírọ, wọn kò sì tún bìkítà fún
niro, won ko si tun bikita fun
wọn.
won.
138. Àwa sì jẹ kí àwọn ẹ̀nìyàn tí
138. Awa si je ki awon eniyan ti
wọn kàkún ẹ̀ẹ̀yàn lásán di àwọn to
won kakun eeyan lasan di awon to
Jogún ìlà-òòrùn ayé àti ìwò-òòrùn
Jogun ila-oorun aye ati iwo-oorun
ayé, ẹ̀yí tí Àwa fi ìbùkún sínú rẹ̀,
aye, eyi ti Awa fi ibukun sinu re,
òrò àánú Olúwa rẹ sì ti ṣẹ lúrí
oro aanu Oluwa re si ti se luri
àwọn ọmọ Israẹli nítorí pé wọn ni
awon omo Israeli nitori pe won ni
ìfaradà, Àwa sì pa gbogbo iṣẹ tí
ifarada, Awa si pa gbogbo ise ti
Fir'aona àti àwọn ẹ̀nìyàn rẹ̀ ṣe run
Fir'aona ati awon eniyan re se run
pẹ̀lú àwọn ilé tí wọn ti kọ.
pelu awon ile ti won ti ko.
139. Àwa sì mú àwọn ọmọ Israẹli la
139. Awa si mu awon omo Israeli la
òkun já, lẹhìn náà wọn (rìn) kàn
okun ja, lehin naa won (rin) kan
àwọn ẹ̀nìyàn kan tí wọn ti fi gbogbo
awon eniyan kan ti won ti fi gbogbo
ọkàn wọn jìn fún àwọn òrìṣà wọn ní
okan won jin fun awon orisa won ni
bíbọ. Wọn wí pé: 'Ìrẹ Musa, ṣe Òrìṣà
bibo. Won wi pe: 'Ire Musa, se Orisa
kan fún àwa náà gẹgẹ bí ti wọn." Oun
kan fun awa naa gege bi ti won." Oun
(Musa) sì sọ pé: 'Dájúdájú ẹ̀yin. jẹ
(Musa) si so pe: 'Dajudaju eyin. je
aláìmòọkan, òpẹ̀ ẹ̀nìyàn.?
alaimookan, ope eniyan.?
“Ninu ogún tìrẹ tí ó bá kàn ọ́ ninu ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín láti gbà, o kò gbọdọ̀ sún ohun tí àwọn baba ńlá rẹ bá fi pààlà ilẹ̀. OLUWA rán Mose pé Ìyà tí ọpọlọpọ ninu yín ti fi jẹ irú ẹni bẹ́ẹ̀ ti tó. Bí ẹ bá ṣe èyí, ẹ óo sọ ilẹ̀ yín di aláìmọ́ nítorí pé ìpànìyàn a máa sọ ilẹ̀ di àìmọ́. Ikú apànìyàn nìkan ni ó sì lè ṣe ètùtù fún ìwẹ̀nùmọ́ ilẹ̀ tí ó ti di àìmọ́ nípa ìpànìyàn. Nítorí OLUWA ń dáàbò bo àwọn olódodo,ṣugbọn àwọn eniyan burúkú yóo ṣègbé.Òdodo rẹ wà títí lae,òtítọ́ sì ni òfin rẹ.Báwo ni n óo ṣe pada dé iwájú baba mi láìmú ọmọ náà lọ́wọ́? Ẹ̀rù ohun burúkú tí yóo ṣẹlẹ̀ sí baba mi, ń bà mí.”Bóyá OLUWA lè wo ìpọ́njú mi, kí ó sì fi ìre dípò èpè tí ó ń ṣẹ́ lé mi.” Saulu dá a lóhùn pé, “Mo mọ̀ pé mo ti ṣẹ̀, ṣugbọn bu ọlá fún mi níwájú àwọn àgbààgbà, àwọn eniyan mi ati gbogbo Israẹli. Bá mi pada lọ, kí n lọ sin OLUWA Ọlọrun rẹ.” Ẹ̀yin tí ń gbé Sioni,ẹ hó, ẹ kọrin ayọ̀, ẹ̀yin olùgbé Sioni,nítorí Ẹni ńlá ni Ẹni Mímọ́ Israẹlití ó wà láàrin yín.”Nítorí náà ni wọ́n ṣe ń pe orúkọ kànga náà ní Beeri-lahai-roi, ó wà láàrin Kadeṣi ati Beredi.Jeremaya wolii bá dá Hananaya wolii lóhùn níṣojú àwọn alufaa ati gbogbo àwọn ará ìlú tí wọn dúró ní ilé OLUWA, Ṣemaaya, àkọ́bí Obedi Edomu, bí ọmọ mẹfa, àwọn ni olórí ninu ìdílé wọn nítorí pé alágbára eniyan ni wọ́n. Josẹfu rí àwọn arakunrin rẹ̀, ó sì mọ̀ wọ́n, ṣugbọn ó bá wọn sọ̀rọ̀ pẹlu ohùn líle bí ẹni pé kò mọ̀ wọ́n rí, ó ní, “Níbo ni ẹ ti wá?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Láti ilẹ̀ Kenaani ni, oúnjẹ ni a wá rà.”Ní ọdún tí Usaya Ọba kú, mo rí OLUWA: ó jókòó lórí ìtẹ́, a gbé e ga sókè, aṣọ ìgúnwà rẹ̀ sì kún inú tẹmpili. Nígbà tí ó gbọ́ ìròyìn ọ̀gágun náà, ó yọ̀ǹda òkú Jesu fún Josẹfu. The scorpion travels accompanied by venom.
“Ninu ogun tire ti o ba kan o ninu ile ti OLUWA Olorun yin fun yin lati gba, o ko gbodo sun ohun ti awon baba nla re ba fi paala ile. OLUWA ran Mose pe Iya ti opolopo ninu yin ti fi je iru eni bee ti to. Bi e ba se eyi, e oo so ile yin di alaimo nitori pe ipaniyan a maa so ile di aimo. Iku apaniyan nikan ni o si le se etutu fun iwenumo ile ti o ti di aimo nipa ipaniyan. Nitori OLUWA n daabo bo awon olododo,sugbon awon eniyan buruku yoo segbe.Ododo re wa titi lae,otito si ni ofin re.Bawo ni n oo se pada de iwaju baba mi laimu omo naa lowo? Eru ohun buruku ti yoo sele si baba mi, n ba mi.”Boya OLUWA le wo iponju mi, ki o si fi ire dipo epe ti o n se le mi.” Saulu da a lohun pe, “Mo mo pe mo ti se, sugbon bu ola fun mi niwaju awon agbaagba, awon eniyan mi ati gbogbo Israeli. Ba mi pada lo, ki n lo sin OLUWA Olorun re.” Eyin ti n gbe Sioni,e ho, e korin ayo, eyin olugbe Sioni,nitori Eni nla ni Eni Mimo Israeliti o wa laarin yin.”Nitori naa ni won se n pe oruko kanga naa ni Beeri-lahai-roi, o wa laarin Kadesi ati Beredi.Jeremaya wolii ba da Hananaya wolii lohun nisoju awon alufaa ati gbogbo awon ara ilu ti won duro ni ile OLUWA, Semaaya, akobi Obedi Edomu, bi omo mefa, awon ni olori ninu idile won nitori pe alagbara eniyan ni won. Josefu ri awon arakunrin re, o si mo won, sugbon o ba won soro pelu ohun lile bi eni pe ko mo won ri, o ni, “Nibo ni e ti wa?”Won da a lohun pe, “Lati ile Kenaani ni, ounje ni a wa ra.”Ni odun ti Usaya Oba ku, mo ri OLUWA: o jokoo lori ite, a gbe e ga soke, aso igunwa re si kun inu tempili. Nigba ti o gbo iroyin ogagun naa, o yonda oku Jesu fun Josefu. The scorpion travels accompanied by venom.
Ṣugbọn bí ó bá jẹ́ pé nípa Ẹ̀mí Ọlọrun ni mo fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a jẹ́ pé ìjọba Ọlọrun ti dé ba yín.Ni Peteru bá tẹ̀lé e jáde. Kò mọ̀ pé òtítọ́ ni ohun tí ó ti ọwọ́ angẹli náà ṣẹlẹ̀, ó ṣebí àlá ni. Nígbà náà ni Miriamu, wolii obinrin, tíí ṣe arabinrin Aaroni, gbé ìlù timbireli lọ́wọ́, gbogbo àwọn obinrin sì tẹ̀lé e, wọ́n ń lu timbireli, wọ́n sì ń jó.Láìpẹ́, àwọn ará Filistia tún wá gbógun ti àwọn tí wọ́n wà ní àfonífojì, wọ́n sì kó wọn lẹ́rú. Kékeré ni èyí tí mo ṣe yìí, n óo máa ṣe jù bí mo ti ṣe yìí lọ. N kò ní jẹ́ nǹkankan lójú rẹ, ṣugbọn àwọn iranṣẹbinrin tí o sọ nípa wọn yìí, yóo bu ọlá fún mi.”Ìyìn ni fún OLUWA, Ọlọrun Israẹli,lae ati laelae.Amin! Amin! 79. Dájúdájú, Olúwa rẹ yúòò ṣe
Sugbon bi o ba je pe nipa Emi Olorun ni mo fi n le awon emi esu jade, a je pe ijoba Olorun ti de ba yin.Ni Peteru ba tele e jade. Ko mo pe otito ni ohun ti o ti owo angeli naa sele, o sebi ala ni. Nigba naa ni Miriamu, wolii obinrin, tii se arabinrin Aaroni, gbe ilu timbireli lowo, gbogbo awon obinrin si tele e, won n lu timbireli, won si n jo.Laipe, awon ara Filistia tun wa gbogun ti awon ti won wa ni afonifoji, won si ko won leru. Kekere ni eyi ti mo se yii, n oo maa se ju bi mo ti se yii lo. N ko ni je nnkankan loju re, sugbon awon iransebinrin ti o so nipa won yii, yoo bu ola fun mi.”Iyin ni fun OLUWA, Olorun Israeli,lae ati laelae.Amin! Amin! 79. Dajudaju, Oluwa re yuoo se
ìpinnu láàrin wọn pẹ̀lú ìdájọ Rẹ̀.
ipinnu laarin won pelu idajo Re.
Òun sì jẹ Alágbára, Olùmọ ohun
Oun si je Alagbara, Olumo ohun
80. Nítorí náà, gbẹkẹ̀lé, Allah,
80. Nitori naa, gbekele, Allah,
hàn gbangba.
han gbangba.
81. Dájúdájú, ìwọ kò le mú kí
81. Dajudaju, iwo ko le mu ki
òkú gbọrọ, bẹ̀ẹ̀ sì ni o kò le mú
oku gboro, bee si ni o ko le mu
adití gbọ ìpé, nígbà tí wọn bá ti
aditi gbo ipe, nigba ti won ba ti
yípadà bìrí.
yipada biri.
82. Bákan náà ni ìwọ kò le tọ
82. Bakan naa ni iwo ko le to
afọjú sọnà kúrò nínú ìṣìnà wọn,
afoju sona kuro ninu isina won,
kìkì àwọn tì o lẹ̀ mú kí wọn
kiki awon ti o le mu ki won
gbòrò ni àwọn tí ô gba Àmì wa
gboro ni awon ti o gba Ami wa
gbọ lododo, tí wQn sì ju ara wọn
gbo lododo, ti wQn si ju ara won
sílẹ̀ (fún Allah).
sile (fun Allah).
83. Nígbà tí ìdájọ ìjìyà náà bá ṣẹ
83. Nigba ti idajo ijiya naa ba se
lé wọn lòri, A ô mú ki ẹ̀dá kan
le won lori, A o mu ki eda kan
Jáde láti inú ilẹ̀ tí yúòò máa pa
Jade lati inu ile ti yuoo maa pa
wọn lára nítorí pé àwọn ẹ̀nìyàn
won lara nitori pe awon eniyan
kò gbàgbò nínú àwọn Àmì Wa.
ko gbagbo ninu awon Ami Wa.
ÌDÁ 7
IDA 7
84. Àti pé ní ọjọ tí A ô kò nínú
84. Ati pe ni ojo ti A o ko ninu
ìran kọọkan, ìjọ kan nínú àwọn tí
iran kookan, ijo kan ninu awon ti
wọn n pe àwọn Àmì Wa nírọ JỌ
won n pe awon Ami Wa niro JO
PỌ, WỌn YyÒÒ sì Wà níjọ-níjọ
PO, WOn YyOO si Wa nijo-nijo
ỌỌỌtỌ.
OOOtO.
85. Títí di ìgbà tí wọn yòò fi dé
85. Titi di igba ti won yoo fi de