diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
oníruurú
oniruuru
Mo sì gba ìwé kékeré náà ni ọwọ́ angẹli náà mo sì jẹ ẹ́ tan; ó sì dùn lẹ́nu mi bí oyin; bí mo sì tí jẹ ẹ́ tan, inú mi korò.
Mo si gba iwe kekere naa ni owo angeli naa mo si je e tan; o si dun lenu mi bi oyin; bi mo si ti je e tan, inu mi koro.
Nígbà tó kàn mí láti jà , ńṣe ni mo kàn dúró gbagidi síbi tá a ti máa ń jà , mi ò lè ṣe nǹkan kan .
Nigba to kan mi lati ja , nse ni mo kan duro gbagidi sibi ta a ti maa n ja , mi o le se nnkan kan .
Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa .
Gbogbo eto je tiwa .
Kàkà bẹ́ẹ̀ , “ ó ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ . ”
Kaka bee , " o se bee gee . "
àwọn omi sì dúró lórí àwọn òkè ńlá
awon omi si duro lori awon oke nla
ṣèbà
seba
Àmọ́ ṣá o , gbogbo ẹ̀ kọ́ ló rọrùn .
Amo sa o , gbogbo e ko lo rorun .
NÍ ỌJỌ́ kan tó bọ́ sígbà ìrúwé ní Ísírẹ́lì ní ọdún 33 Sànmánì Tiwa , àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù kóra jọ sórí òkè ńlá kan ní Gálílì .
NI OJO kan to bo sigba iruwe ni Isireli ni odun 33 Sanmani Tiwa , awon omo eyin Jesu kora jo sori oke nla kan ni Galili .
Ó da Ẹ̀mí yìí lé wa lórí lọpọlọpọ láti ọwọ́ Jesu Kristi Olùgbàlà wa.
O da Emi yii le wa lori lopolopo lati owo Jesu Kristi Olugbala wa.
yàtọ̀ sí èmi kò sí ọlọ́run kan, Èmi yóò fún ọ ní okun, bí o kò tilẹ̀ tí ì gbà mí, tí o fi jẹ́ pé láti ìlà oòrùn títí dé ibi ìwọ̀ rẹ̀ kí ènìyàn le mọ̀, kò sí ẹnìkan lẹ́yìn mi
yato si emi ko si olorun kan, Emi yoo fun o ni okun, bi o ko tile ti i gba mi, ti o fi je pe lati ila oorun titi de ibi iwo re ki eniyan le mo, ko si enikan leyin mi
Jèhófà máa jẹ́ ìpín wa tá a bá fi iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ sípò àkọ́kọ́
Jehofa maa je ipin wa ta a ba fi ise isin re sipo akoko
Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ń gbé ní Sìǹbábúwè kọ̀wé pé : “ A dúpẹ́ gan - an lọ́wọ́ gbogbo àwọn ará lọ́kùnrin lóbìnrin tí wọ́n wá láti ọ̀pọ̀ orílẹ̀ - èdè láti bá wa kọ́ àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba tó lẹ́wà ní Sìǹbábúwè .
Elerii Jehofa kan to n gbe ni Sinbabuwe kowe pe : " A dupe gan - an lowo gbogbo awon ara lokunrin lobinrin ti won wa lati opo orile - ede lati ba wa ko awon Gbongan Ijoba to lewa ni Sinbabuwe .
17. Ti wọn n fi ara hàn tí wọn tún
17. Ti won n fi ara han ti won tun
“Nítorí náà sọ fún ilé Israẹli pé: ‘Èyí ní ohun tí Olódùmarè wí: Ṣé o fẹ́ ba ara rẹ jẹ́ bi àwọn baba rẹ ṣe ṣe, tiwọn ń ṣe àgbèrè nípa títẹ̀lé àwọn àwòrán ìríra?
“Nitori naa so fun ile Israeli pe: ‘Eyi ni ohun ti Olodumare wi: Se o fe ba ara re je bi awon baba re se se, tiwon n se agbere nipa titele awon aworan irira?
Ẹ jẹ́ ká tẹ̀ lé ìmọ̀ràn tó wà nínú 1 Kọ́ríńtì 10 : 12 , ká má sì ṣe dá ara wa lójú jù .
E je ka te le imoran to wa ninu 1 Korinti 10 : 12 , ka ma si se da ara wa loju ju .
Ìgbìmọ̀ Tó Túmọ̀ Bíbélì Ayé Tuntun ò sì jẹ́ kóyán irú orúkọ pàtàkì bẹ́ẹ̀ kéré láé débi táá fi yọ ọ́ kúrò nínú Bíbélì .
Igbimo To Tumo Bibeli Aye Tuntun o si je koyan iru oruko pataki bee kere lae debi taa fi yo o kuro ninu Bibeli .
( a ) Kí làwọn ìwé tí Jésù kọ sí ìjọ méje tó wà ní Éṣíà Kékeré fi hàn nípa Jésù ?
( a ) Ki lawon iwe ti Jesu ko si ijo meje to wa ni Esia Kekere fi han nipa Jesu ?
Alábùkún fún ni ẹ̀yin tí ń sọkún nísinsin yìí
Alabukun fun ni eyin ti n sokun nisinsin yii
13 March 2016.
13 March 2016.
Ẹnikẹ́ni ò tòògbé tàbí sùn
Enikeni o toogbe tabi sun
Àmọ́ o , ìgbà wo ni ẹnì kan máa ń di òjíṣẹ́ ?
Amo o , igba wo ni eni kan maa n di ojise ?
“ Lo Ìgbàgbọ́ ”
“ Lo Igbagbo ”
Ẹ̀mí Mímọ́ lè fún ẹnìkan ní ọgbọ́n láti lè fún ènìyàn lámọ́ràn, ẹlòmíràn ní ẹ̀bùn láti sọ̀rọ̀ pẹ̀lú ìmọ̀ ńlá
Emi Mimo le fun enikan ni ogbon lati le fun eniyan lamoran, elomiran ni ebun lati soro pelu imo nla
Ni àwọn ìwé ìròyìn náà bá tún bẹ̀rẹ̀ sí dé sí àdírẹ́sì wa tuntun , mi ò sì tíì já ìkankan wò rárá kúrò nínú bébà tí wọ́n fi dì í wá .
Ni awon iwe iroyin naa ba tun bere si de si adiresi wa tuntun , mi o si tii ja ikankan wo rara kuro ninu beba ti won fi di i wa .
Ẹrù tóun alára rù ni , ìyẹn àǹfààní ṣíṣe ìfẹ́ Ọlọ́run .
Eru toun alara ru ni , iyen anfaani sise ife Olorun .
Ṣé irin yẹn ṣì wà níbẹ , tó sì dúró sán - ún ?
Se irin yen si wa nibe , to si duro san - un ?
Ọdún 1945 ni ogun náà parí .
Odun 1945 ni ogun naa pari .
Ṣùgbọ́n , o wá lè béèrè pé , ‘ bí ikú tí Jésù kú ní nǹkan bí ẹgbàá [ 2,000 ] ọdún sẹ́yìn bá ti mú kó ṣeé ṣe fún ìran èèyàn láti padà di ẹni pípé , kí ló wá dé tí ìwà ibi àti ikú ṣì wà títí dòní olónìí ? ’
Sugbon , o wa le beere pe , ‘ bi iku ti Jesu ku ni nnkan bi egbaa [ 2,000 ] odun seyin ba ti mu ko see se fun iran eeyan lati pada di eni pipe , ki lo wa de ti iwa ibi ati iku si wa titi doni olonii ? ’
Ẹ jẹ́ kí odo kí ó sápẹ́, ẹ jẹ́ kí òkè kí o kọrin pẹ̀lú ayọ̀
E je ki odo ki o sape, e je ki oke ki o korin pelu ayo
Sàárè , ìyẹn isà òkú sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn pẹ́kípẹ́kí , ó sì ń ṣekú pa omilẹgbẹ èèyàn ! ​ — Ìṣípayá 6 : 1 - 8 .
Saare , iyen isa oku si n to o leyin pekipeki , o si n seku pa omilegbe eeyan ! -- Isipaya 6 : 1 - 8 .
Wọ́n fún gbogbo àwọn ẹranko igbó ní omiàwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ń pa òǹgbẹ wọn.
Won fun gbogbo awon eranko igbo ni omiawon ketekete n pa ongbe won.
Àwọn òpìtàn bíi Josephus àti Tacitus tó gbé láyé ní ọgọ́rùn - ún ọdún kìíní dárúkọ Jésù pé ó gbé ayé rí lóòótọ́ .
Awon opitan bii Josephus ati Tacitus to gbe laye ni ogorun - un odun kiini daruko Jesu pe o gbe aye ri loooto .
“Àlejò kan sì tọ ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà wá, òun kò sì fẹ́ mú nínú àgùntàn rẹ̀, àti nínú màlúù rẹ̀: láti fi ṣe àlejò fún ẹni tí ó tọ̀ ọ́ wá: o sì mú àgùntàn ọkùnrin tálákà náà fi ṣe àlejò fún ọkùnrin tí ó tọ̀ ọ́ wá.”
"Alejo kan si to okunrin oloro naa wa, oun ko si fe mu ninu aguntan re, ati ninu maluu re: lati fi se alejo fun eni ti o to o wa: o si mu aguntan okunrin talaka naa fi se alejo fun okunrin ti o to o wa."
Èyĩ ni ìgbà nã tí ìrora nwọn
Eyi ni igba na ti irora nwon
Nígbà tí Mata ti sọ báyìí tán, ó lọ pe Maria arabinrin rẹ̀ sí ìkọ̀kọ̀. Ó ní, “Olùkọ́ni ti dé, ó ń pè ọ́.”
Nigba ti Mata ti so bayii tan, o lo pe Maria arabinrin re si ikoko. O ni, “Olukoni ti de, o n pe o.”
Ṣugbọn ó kọ ìmọ̀ràn tí àwọn àgbààgbà fún un. Kàkà bẹ́ẹ̀, ó jíròrò pẹlu àwọn ọdọmọkunrin, ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, tí wọ́n jọ dàgbà pọ̀, tí wọ́n wà ní ààfin pẹlu rẹ̀.
Sugbon o ko imoran ti awon agbaagba fun un. Kaka bee, o jiroro pelu awon odomokunrin, elegbe re, ti won jo dagba po, ti won wa ni aafin pelu re.
Àwọn náà á sì lè jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ tí onísáàmù sọ pé : “ Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìrànlọ́wọ́ mi ti wá . ” — Sáàmù 121 : 2 .
Awon naa a si le jerii si oro ti onisaamu so pe : " Odo Jehofa ni iranlowo mi ti wa . " -- Saamu 121 : 2 .
Àwọn wọ̀nyí ń retí ìmúṣẹ ìdájọ́ Ọlọ́run lórí àwọn èèyàn burúkú , ó sì dájú pé àwọn ni ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ń bá wí , èyí tó sọ pé : “ ‘ Ẹ máa wà ní ìfojúsọ́nà fún mi , ’ ni àsọjáde Jèhófà , ‘ títí di ọjọ́ tí èmi yóò dìde sí ẹrù àkótogunbọ̀ , nítorí ìpinnu ìdájọ́ mi ni láti kó àwọn orílẹ̀ - èdè jọ , kí n kó àwọn ìjọba jọpọ̀ , kí n lè da ìdálẹ́bi tí ó ti ọ̀dọ̀ mi wá jáde sórí wọn , gbogbo ìbínú jíjófòfò mi ; nítorí nípa iná ìtara mi , gbogbo ilẹ̀ ayé ni a ó jẹ run . ’ ” — Sefanáyà 3 : 8 .
Awon wonyi n reti imuse idajo Olorun lori awon eeyan buruku , o si daju pe awon ni oro wonyi n ba wi , eyi to so pe : " ' E maa wa ni ifojusona fun mi , ' ni asojade Jehofa , ' titi di ojo ti emi yoo dide si eru akotogunbo , nitori ipinnu idajo mi ni lati ko awon orile - ede jo , ki n ko awon ijoba jopo , ki n le da idalebi ti o ti odo mi wa jade sori won , gbogbo ibinu jijofofo mi ; nitori nipa ina itara mi , gbogbo ile aye ni a o je run . ' " -- Sefanaya 3 : 8 .
Wòlíì Aísáyà sọ ojú tí Ọlọ́run fi wo ìwà àìṣòótọ́ yìí , ó ní : “ Ẹ̀yin jẹ́ àwọn tí ń fi Jèhófà sílẹ̀ , àwọn tí ń gbàgbé òkè ńlá mímọ́ mi , àwọn tí ń tẹ́ tábìlì fún ọlọ́run Oríire , àti àwọn tí ń bu àdàlù wáìnì kún dẹ́nu fún ọlọ́run Ìpín . ”
Wolii Aisaya so oju ti Olorun fi wo iwa aisooto yii , o ni : “ Eyin je awon ti n fi Jehofa sile , awon ti n gbagbe oke nla mimo mi , awon ti n te tabili fun olorun Oriire , ati awon ti n bu adalu waini kun denu fun olorun Ipin . ”
Torí náà , ọwọ́ rẹ ló kù sí láti má ṣe gba ẹnikẹ́ni láyè láti ba ìṣọ̀kan tó wà láàárín ìwọ àti ọkọ tàbí aya rẹ jẹ́ .
Tori naa , owo re lo ku si lati ma se gba enikeni laye lati ba isokan to wa laaarin iwo ati oko tabi aya re je .
Rọra tẹ èso náà .
Rora te eso naa .
Ìtàn ìgbésí ayé Emmanuel Lionoudakis wà nínú Ilé Ìṣọ́ , September 1 , 1999 , ojú ìwé 25 sí 29 .
Itan igbesi aye Emmanuel Lionoudakis wa ninu Ile Iso , September 1 , 1999 , oju iwe 25 si 29 .
wọn nínú rere ṣíṣe, wọn n ké pẹ̀ Wá
won ninu rere sise, won n ke pe Wa
Torí pé ìfẹ́ Jèhófà kì í yẹ̀ , ó dá wa lójú pé Jèhófà á dúró tì wá , á sì ràn wá lọ́wọ́ láti borí àwọn ohun tó lè mú ká dẹ́ṣẹ̀ .
Tori pe ife Jehofa ki i ye , o da wa loju pe Jehofa a duro ti wa , a si ran wa lowo lati bori awon ohun to le mu ka dese .
ibò
ibo
Tẹ́ wa lọ́rùn ní òwúrọ̀ nínú ìṣeun ìfẹ́ rẹ,kí àwa kí ó lè kọrin fún ayọ̀kí inú wa sì dùn ní gbogbo ọjọ́.
Te wa lorun ni owuro ninu iseun ife re,ki awa ki o le korin fun ayoki inu wa si dun ni gbogbo ojo.
Robertson sọ pé : “ Kò sí ẹsẹ méjèèjì yìí nínú ìwé àfọwọ́kọ Bíbélì tó lọ́jọ́ lórí jù , tó sì péye jù lọ .
Robertson so pe : “ Ko si ese mejeeji yii ninu iwe afowoko Bibeli to lojo lori ju , to si peye ju lo .
Bí àpẹẹrẹ , Ábúráhámù máa ń lo ọ̀rọ̀ náà , “ jọ̀wọ́ , ” fún Sárà .
Bi apeere , Aburahamu maa n lo oro naa , " jowo , " fun Sara .
Jehoiakimu ọba gba owó orí lọ́wọ́ àwọn eniyan gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ wọn ti pọ̀ tó, láti rí owó san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba Ijipti gẹ́gẹ́ bí ó ti pa á láṣẹ fún un.
Jehoiakimu oba gba owo ori lowo awon eniyan gege bi oro won ti po to, lati ri owo san isakole fun oba Ijipti gege bi o ti pa a lase fun un.
Àmọ́ , kí ni ìyẹn túmọ̀ sí ?
Amo , ki ni iyen tumo si ?
dájúdájú. Allah kò fẹràn. àwọn
dajudaju. Allah ko feran. awon
Ti ìgbà ìkẹyìn ni bó ṣe fi àìmọtara ẹni nìkan sọ ara rẹ̀ di mímọ̀ fún Bóásì , tó dàgbà jù ú fíìfíì , nítorí pé ó jẹ́ olùtúnnirà .
Ti igba ikeyin ni bo se fi aimotara eni nikan so ara re di mimo fun Boasi , to dagba ju u fiifii , nitori pe o je olutunnira .
Ẹni tí kò ṣe déédé nínú iṣẹ́ rẹ̀ arákùnrin ló jẹ́ fún apanirun
Eni ti ko se deede ninu ise re arakunrin lo je fun apanirun
Ran Akẹ́kọ̀ọ́ Lọ́wọ́ Láti Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà
Ran Akekoo Lowo Lati Di Ore Jehofa
Mo tiraka láti jáwọ́ nínú lílo oògùn olóró , mo sì tún bẹ̀rẹ̀ sí í lọ síbi tá a ti máa ń kọ́ ìjà kọnfú .
Mo tiraka lati jawo ninu lilo oogun oloro , mo si tun bere si i lo sibi ta a ti maa n ko ija konfu .
Ó ṣeni láàánú pé , àwọn ọkùnrin yìí tí wọ́n wá láti ilé rere , tí wọ́n sì tún láǹfààní láti ṣe ohun tí ó tọ́ fi ogún tẹ̀mí wọn ṣòfò !
O seni laaanu pe , awon okunrin yii ti won wa lati ile rere , ti won si tun lanfaani lati se ohun ti o to fi ogun temi won sofo !
Yálà à ń retí láti gbé lókè ọ̀run tàbí lórí ilẹ̀ ayé , ẹ jẹ́ ká kọ́ ẹ̀kọ́ pàtàkì tó wà nínú àkàwé àwọn wúńdíá mẹ́wàá náà .
Yala a n reti lati gbe loke orun tabi lori ile aye , e je ka ko eko pataki to wa ninu akawe awon wundia mewaa naa .
Nígbà tí Reubeni padà dé ibi kòtò tí ó sì ri pé Josẹfu kò sí níbẹ̀ mọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya pẹ̀lú ìbànújẹ́.
Nigba ti Reubeni pada de ibi koto ti o si ri pe Josefu ko si nibe mo, o fa aso re ya pelu ibanuje.
Ọdún mẹ́rin kọjá , Jòsáyà sì dáwọ́ lé rírẹ́yìn ìsìn èké ní Júdà òun Jerúsálẹ́mù ( 648 ṣááju Sànmánì Tiwa ) .
Odun merin koja , Josaya si dawo le rireyin isin eke ni Juda oun Jerusalemu ( 648 saaju Sanmani Tiwa ) .
Ìbẹ̀rù OLUWA a máa mú kí ẹ̀mí eniyan gùn,ṣugbọn ìgbé ayé eniyan burúkú yóo kúrú.
Iberu OLUWA a maa mu ki emi eniyan gun,sugbon igbe aye eniyan buruku yoo kuru.
Síbẹ̀ , ó ti mú kó rọrùn láti tètè rí àwọn ọ̀rọ̀ kan tá à ń wá tàbí ká fa ilà sí àwọn ẹsẹ tọ́rọ̀ inú rẹ̀ máa ń wọ̀ wá lọ́kàn .
Sibe , o ti mu ko rorun lati tete ri awon oro kan ta a n wa tabi ka fa ila si awon ese toro inu re maa n wo wa lokan .
Nínú 1 Tímótì 5 : 8 , kí ni Pọ́ọ̀lù ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé káwọn òbí pèsè fún ìdílé ?
Ninu 1 Timoti 5 : 8 , ki ni Poolu ni lokan nigba to so pe kawon obi pese fun idile ?
Kí ló máa fi hàn pé ẹnì kan jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn Jésù Kristi ?
Ki lo maa fi han pe eni kan je omo eyin Jesu Kristi ?
Ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run lè fún ẹ lókun tó máa jẹ́ kó o lè jáwọ́ nínú àwọn ìwà tó ń pani lára .
Emi mimo Olorun le fun e lokun to maa je ko o le jawo ninu awon iwa to n pani lara .
Lámékì kọ orin ewì kan nípa pípa tó pa ọ̀dọ́mọkùnrin kan , ó lòun gbẹ̀mí ẹ̀ láti lè dáàbò bo ara òun , èyí tó fi irú ìwà táwọn èèyàn ń hù láyé ìgbà náà hàn .
Lameki ko orin ewi kan nipa pipa to pa odomokunrin kan , o loun gbemi e lati le daabo bo ara oun , eyi to fi iru iwa tawon eeyan n hu laye igba naa han .
Lóòótọ́ , kò rọrùn láti máa fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò , àmọ́ ó dá mi lójú pé èyí gan - an lọ̀nà tó dáa jù lọ láti gbé ìgbésí ayé ẹni .
Loooto , ko rorun lati maa fi awon ilana Bibeli silo , amo o da mi loju pe eyi gan - an lona to daa ju lo lati gbe igbesi aye eni .
Gbogbo àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró lọ́kùnrin lóbìnrin ló ń kópa nínú iṣẹ́ sísọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn .
Gbogbo awon Kristeni eni ami ororo lokunrin lobinrin lo n kopa ninu ise siso awon eeyan di omo eyin .
Torí náà , bó bá jẹ́ pé a fẹ́ di òmìnira ní tòótọ́ , ìyẹn ni pé ká lè máa ṣe ohun tó wà lọ́kàn wa , ńṣe ló yẹ ká máa ní èrò rere lọ́kàn , èrò tí kò ní ta ko irú ẹni tí Jèhófà jẹ́ àti àwọn ìlànà rẹ̀ .
Tori naa , bo ba je pe a fe di ominira ni tooto , iyen ni pe ka le maa se ohun to wa lokan wa , nse lo ye ka maa ni ero rere lokan , ero ti ko ni ta ko iru eni ti Jehofa je ati awon ilana re .
Lóòótọ́ , ẹ̀rí ọkàn tó ń dáni lẹ́bi dà bí ẹrù tó wúwo téèyàn ń gbé kiri .
Loooto , eri okan to n dani lebi da bi eru to wuwo teeyan n gbe kiri .
Ìròyìn náà wá sọ pé “ táṣejù bá ti wọ iye àkókò téèyàn fi ń ṣiṣẹ́ , ńṣe ni bó ṣe yẹ káwọn òṣìṣẹ́ ṣe dáadáa sí máa ń dín kù , tí ṣíṣeé ṣe pé kéèyàn ṣàṣìṣe yóò sì máa ga sí i . ”
Iroyin naa wa so pe " taseju ba ti wo iye akoko teeyan fi n sise , nse ni bo se ye kawon osise se daadaa si maa n din ku , ti sisee se pe keeyan sasise yoo si maa ga si i . "
abẹ́rẹ́
abere
Ìdí ni pé Jónátánì jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà ó sì lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ , àmọ́ Ábínérì ò lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ kì í sì í ṣe adúróṣinṣin .
Idi ni pe Jonatani je adurosinsin si Jehofa o si lemii irele , amo Abineri o lemii irele ki i si i se adurosinsin .
Àwọn alàgbà náà tún sọ èrò tẹ́nì kọ̀ọ̀kan wọ́n ní lórí ọ̀rọ̀ ìdádọ̀dọ́ .
Awon alagba naa tun so ero teni kookan won ni lori oro idadodo .
Bóyá o ronú pé wọn kò ní lóye ìṣòro rẹ dáadáa .
Boya o ronu pe won ko ni loye isoro re daadaa .
Nínú iṣẹ́ yìí a ṣe àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ ọnà àtinúdá bì i ewì ní pàtàkì jùlọ oríkì láwùjọ Yorùbá. Iṣẹ́ yìí tan iná wo oríkì tí a le bá pàdé láwùjọ Yorùbá bí i; oríkì orílẹ̀ àti ti ọba. Ṣe okùn kì í gùn kò má ni ibi tí a fàá wà. Iṣẹ́ yìí tọpinpin orírun ìlú Òǹdó tí a ń gbéyẹ̀wò ìdílé kọ̀ọ̀kan tó ti jẹ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ títí di òní.
Ninu ise yii a se agbeyewo ise ona atinuda bi i ewi ni pataki julo oriki lawujo Yoruba. Ise yii tan ina wo oriki ti a le ba pade lawujo Yoruba bi i; oriki orile ati ti oba. Se okun ki i gun ko ma ni ibi ti a faa wa. Ise yii topinpin orirun ilu Ondo ti a n gbeyewo idile kookan to ti je lati ibere pepe titi di oni.
Ọ̀rọ̀ rẹ̀ ń tù wá nínú , ó sì ń ràn wá lọ́wọ́ láti fi ìrètí àjíǹde tó lágbára tu àwọn mìíràn nínú .
Oro re n tu wa ninu , o si n ran wa lowo lati fi ireti ajinde to lagbara tu awon miiran ninu .
“ BÍ A bá yẹ àwọn ìlú ńlá wa wò , ọjọ́ ọ̀la wa là ń yẹ̀ wò yẹn . ”
" BI A ba ye awon ilu nla wa wo , ojo ola wa la n ye wo yen . "
Má ṣe jẹ́ kí tafàtafà yọ ọfà rẹ̀jáde tàbí kí ó di ìhámọ́ra rẹ̀;má ṣe dá àwọn ọ̀dọ́mọkùnrinsí, pátápátá ni kí o pa àwọn ọmọ-ogun rẹ̀.
Ma se je ki tafatafa yo ofa rejade tabi ki o di ihamora re;ma se da awon odomokunrinsi, patapata ni ki o pa awon omo-ogun re.
Wákàtí kan àti ìṣẹ́jú mẹ́ẹ̀dógún
Wakati kan ati iseju meedogun
Ọ̀pọ̀ àwọn tó máa ń ṣàlàyé ọ̀ràn òfin ti ṣàyẹ̀wò àkọsílẹ̀ ìgbẹ́jọ́ Jésù nínú ìwé Ìhìn Rere .
Opo awon to maa n salaye oran ofin ti sayewo akosile igbejo Jesu ninu iwe Ihin Rere .
Ní àfẹ̀mọ́jú, àwọn ańgẹ́lì náà rọ Lọ́tì pé, Ṣe wéré, mú aya rẹ àti àwọn ọmọbìnrin rẹ méjèèjì tí ó wà níhìnín, àìṣe bẹ́ẹ̀, ìwọ yóò parun pẹ̀lú ìlú yìí nígbà tí wọ́n bá ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn
Ni afemoju, awon angeli naa ro Loti pe, Se were, mu aya re ati awon omobinrin re mejeeji ti o wa nihinin, aise bee, iwo yoo parun pelu ilu yii nigba ti won ba n jiya ese won
Tó bá jẹ́ pé “ ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ ” tàbí “ ìṣẹ̀fẹ̀ rírùn ” ló máa ń tẹnu ọmọdébìnrin yìí jáde tẹ́lẹ̀ , ǹjẹ́ ì bá rọrùn fún un láti lo ahọ́n rẹ̀ lọ́nà tó gbéṣẹ́ bẹ́ẹ̀ nígbà tí àǹfààní rẹ̀ ṣí sílẹ̀ ?
To ba je pe “ oro omugo ” tabi “ isefe rirun ” lo maa n tenu omodebinrin yii jade tele , nje i ba rorun fun un lati lo ahon re lona to gbese bee nigba ti anfaani re si sile ?
Ó kà pé : “ Kí olúkúlùkù yín lẹ́nì kọ̀ọ̀kan máa nífẹ̀ẹ́ aya rẹ̀ bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe nífẹ̀ẹ́ ara rẹ̀ ; ní ọwọ́ kejì ẹ̀wẹ̀ , kí aya ní ọ̀wọ̀ jíjinlẹ̀ fún ọkọ rẹ̀ . ”
O ka pe : " Ki olukuluku yin leni kookan maa nifee aya re bee gege bi o se nifee ara re ; ni owo keji ewe , ki aya ni owo jijinle fun oko re . "
Bọ́lá : Ẹ ṣeun .
Bola : E seun .
Látinú Ìwé The Parallel Bible , The Holy Bible , 1885
Latinu Iwe The Parallel Bible , The Holy Bible , 1885
Nígbà ti wọ́n padà sí Jerusalẹmu, ó wọ inú tẹmpili. Ó bẹ̀rẹ̀ sí nílé àwọn oníṣòwò àti àwọn oníbàárà wọn síta. Ó ti tábìlì àwọn tí ń pààrọ̀ owó nínú tẹmpili ṣubú. Bákan náà ni ó ti ìjókòó àwọn tí ń ta ẹyẹlé lulẹ̀.
Nigba ti won pada si Jerusalemu, o wo inu tempili. O bere si nile awon onisowo ati awon onibaara won sita. O ti tabili awon ti n paaro owo ninu tempili subu. Bakan naa ni o ti ijokoo awon ti n ta eyele lule.
ṣọ́bìrì
sobiri
astárótì
astaroti
Ìdájọ́ Ọlọ́run
Idajo Olorun
Ohun tí àwọn òbí rẹ , àwọn ọ̀rẹ́ rẹ , àti àwọn olùkọ́ rẹ ń retí pé kí o ṣe ; bí ara àti ìmọ̀lára rẹ ṣe ń yí padà nígbà ìbàlágà ; tàbí ríronú pé o kò lè dá nǹkan kan ṣe láṣeyọrí nítorí àwọn àṣìṣe pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́ tí o ń ṣe — gbogbo nǹkan wọ̀nyí lè kó ìrẹ̀wẹ̀sì àti ìbànújẹ́ bá ọ .
Ohun ti awon obi re , awon ore re , ati awon oluko re n reti pe ki o se ; bi ara ati imolara re se n yi pada nigba ibalaga ; tabi rironu pe o ko le da nnkan kan se laseyori nitori awon asise peepeepe ti o n se -- gbogbo nnkan wonyi le ko irewesi ati ibanuje ba o .
Yíyàn tí Ọlọ́run ń yan àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró ń bá a lọ ní gbogbo ìgbà táwọn àpọ́sítélì fi wà láyé , ṣùgbọ́n lẹ́yìn ikú àwọn àpọ́sítélì ìwọ̀nba díẹ̀ làwọn tí Ọlọ́run yàn .
Yiyan ti Olorun n yan awon Kristeni eni ami ororo n ba a lo ni gbogbo igba tawon apositeli fi wa laye , sugbon leyin iku awon apositeli iwonba die lawon ti Olorun yan .
Kódà , bá a bá rò pé eré ìdárayá kan kò burú , tá a sì ń lo àkókò tó pọ̀ jù láti máa wo eré ìdárayá náà , ìyẹn pẹ̀lú lè máa gba àkókò tó yẹ ká lò fún ìjọsìn ìdílé , kíka Bíbélì lójoojúmọ́ àti mímúra sílẹ̀ fáwọn ìpàdé . — Fílí .
Koda , ba a ba ro pe ere idaraya kan ko buru , ta a si n lo akoko to po ju lati maa wo ere idaraya naa , iyen pelu le maa gba akoko to ye ka lo fun ijosin idile , kika Bibeli lojoojumo ati mimura sile fawon ipade . — Fili .
Síbẹ̀ , ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn jàǹdùkú tó wà lẹ́wọ̀n ló sá lọ nígbà tí ìsẹ̀lẹ̀ yẹn mú kí ògiri ọgbà ẹ̀wọ̀n tí wọ́n wà wó lulẹ̀ .
Sibe , egbeegberun awon janduku to wa lewon lo sa lo nigba ti isele yen mu ki ogiri ogba ewon ti won wa wo lule .
kí gbogbo àwọn tí ó yíi ká mú ẹ̀bùn wá fún ẹni tí o tọ́ láti bẹ̀rù
ki gbogbo awon ti o yii ka mu ebun wa fun eni ti o to lati beru
Bí àìsàn bára kú bá ń ṣe ẹnì kan nínú ìdílé , ọ̀pọ̀ nǹkan tí ìdílé náà ń ṣe á ṣì wà láìyípadà .
Bi aisan bara ku ba n se eni kan ninu idile , opo nnkan ti idile naa n se a si wa laiyipada .
Ó mọ bó ṣe lè lo àwọn ohun àmúṣọrọ̀ tó wà lórí ilẹ̀ ayé , kó ṣèkáwọ́ rẹ̀ , kó sì lò ó fún àǹfààní aráyé ní ọgbọọgba àti lọ́nà tó tọ́ .
O mo bo se le lo awon ohun amusoro to wa lori ile aye , ko sekawo re , ko si lo o fun anfaani araye ni ogboogba ati lona to to .
Ẹsẹ yẹn kà pé : “ Ọmọ ènìyàn ti wá , kì í ṣe kí a lè ṣe ìránṣẹ́ fún un , bí kò ṣe kí ó lè ṣe ìránṣẹ́ , kí ó sì fi ọkàn rẹ̀ fúnni gẹ́gẹ́ bí ìràpadà ní pàṣípààrọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn . ”
Ese yen ka pe : “ Omo eniyan ti wa , ki i se ki a le se iranse fun un , bi ko se ki o le se iranse , ki o si fi okan re funni gege bi irapada ni pasipaaro fun opolopo eniyan . ”
Nínú ìwé ìròyìn Canadian Geographic , Katharine Vansittart sọ pé : “ Oríṣi irè oko kan làwọn tó máa ń dá oko rẹpẹtẹ máa ń fẹ́ láti gbìn lọ́pọ̀ jaburata , ohun tó sì ń jẹ́ kó ṣeé ṣe fún wọn láti mú ọ̀pọ̀ irè jáde ni lílo ẹ̀rọ , oògùn apakòkòrò àti ajílẹ̀ .
Ninu iwe iroyin Canadian Geographic , Katharine Vansittart so pe : " Orisi ire oko kan lawon to maa n da oko repete maa n fe lati gbin lopo jaburata , ohun to si n je ko see se fun won lati mu opo ire jade ni lilo ero , oogun apakokoro ati ajile .
“ Títàbùkù àwọn ẹlẹ́wọ̀n àti ṣíṣe wọ́n níṣekúṣe kọ́ ló máa mú kí wọ́n di ọmọlúwàbí bí wọ́n bá jáde lẹ́wọ̀n . ” — Ọ̀RỌ̀ OLÓÒTÚ NÍNÚ ÌWÉ ÌRÒYÌN THE ATLANTA CONSTITUTION .
" Titabuku awon elewon ati sise won nisekuse ko lo maa mu ki won di omoluwabi bi won ba jade lewon . " -- ORO OLOOTU NINU IWE IROYIN THE ATLANTA CONSTITUTION .