diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
( b ) Báwo ni Ábúráhámù ṣe fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ nípa gbígbé ìgbésí ayé rẹ̀ ka ìgbàgbọ́ nínú àwọn ìlérí Ọlọ́run ? | ( b ) Bawo ni Aburahamu se fi apeere rere lele nipa gbigbe igbesi aye re ka igbagbo ninu awon ileri Olorun ? |
Ìfẹ́ tí mo rí nínú ìjọ yẹn gan - an ló mú un dá mi lójú pé òtítọ́ nìyí , mo sì ṣe ìrìbọmi lọ́dún 1960 . ” | Ife ti mo ri ninu ijo yen gan - an lo mu un da mi loju pe otito niyi , mo si se iribomi lodun 1960 . ” |
Kí ni nǹkan ọ̀hún ? | Ki ni nnkan ohun ? |
Ní ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà , inú wọn á ṣì máa dùn bí wọ́n ti ń rí i pé àgọ́ ìjọsìn náà ṣì wúlò fún iṣẹ́ ìsìn Jèhófà . | Ni opo odun leyin naa , inu won a si maa dun bi won ti n ri i pe ago ijosin naa si wulo fun ise isin Jehofa . |
Bí a ṣe kẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ nínú àpilẹ̀kọ tó ṣáájú èyí , Jèhófà Ọlọ́run àti Ábúráhámù ìránṣẹ́ rẹ̀ olódodo búra láwọn àkókò pàtàkì kan . | Bi a se kekoo re ninu apileko to saaju eyi , Jehofa Olorun ati Aburahamu iranse re olododo bura lawon akoko pataki kan . |
Bí mo ṣe ń dàgbà ni mo túbọ̀ ń nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́ . | Bi mo se n dagba ni mo tubo n nifee si otito . |
Rárá o , Jésù fi àpẹẹrẹ pípé lélẹ̀ nípa wíwà ní ìwọ̀ntúnwọ̀nsì . | Rara o , Jesu fi apeere pipe lele nipa wiwa ni iwontunwonsi . |
Ọgọ́rùn - ún ọdún kẹta ni wọ́n ṣe èyí tọ́jọ́ rẹ̀ pẹ́ jù lọ nínú àwọn ère tí wọ́n gbẹ́ sínú àwọn ibojì abẹ́lẹ̀ yìí . | Ogorun - un odun keta ni won se eyi tojo re pe ju lo ninu awon ere ti won gbe sinu awon iboji abele yii . |
Àwọn èèyàn máa ń sọ pé , ‘ olówó layé mọ̀ . ’ | Awon eeyan maa n so pe , ' olowo laye mo . ' |
Nígbà tí wọn kò rí ọ̀nà ati san gbèsè wọn, ẹni tí ó yá wọn lówó bùn wọ́n ní owó náà. Ninu àwọn mejeeji, ta ni yóo fẹ́ràn rẹ̀ jù?” | Nigba ti won ko ri ona ati san gbese won, eni ti o ya won lowo bun won ni owo naa. Ninu awon mejeeji, ta ni yoo feran re ju?" |
ó sì di àmùrè ẹ̀gbẹ́ rẹ, ó sì ṣáré níwájú Áhábù títí dé Jésírẹ́lì | o si di amure egbe re, o si sare niwaju Ahabu titi de Jesireli |
( b ) Kí la máa jíròrò nínú àpilẹ̀kọ yìí àti èyí tó kàn ? | ( b ) Ki la maa jiroro ninu apileko yii ati eyi to kan ? |
Ìwé náà , Diabetes — Caring for Your Emotions as Well as Your Health ṣàlàyé pé : “ Bó o bá gbìyànjú láti mọ gbogbo ohun tó so mọ́ àrùn náà lẹ́ẹ̀kan , ó ṣeé ṣe kó o máà rí ojútùú rẹ̀ kó o má sì lè lo àwọn ìsọfúnni tó o rí náà lọ́nà tó máa ṣe ọ́ láǹfààní . | Iwe naa , Diabetes — Caring for Your Emotions as Well as Your Health salaye pe : “ Bo o ba gbiyanju lati mo gbogbo ohun to so mo arun naa leekan , o see se ko o maa ri ojutuu re ko o ma si le lo awon isofunni to o ri naa lona to maa se o lanfaani . |
“ Ká sòótọ́ , ibẹ̀ yẹn dùn jọ̀ọ́ — ìgbádùn rẹpẹtẹ wà níbẹ̀ ! | " Ka sooto , ibe yen dun joo -- igbadun repete wa nibe ! |
tí ẹ̀yin bá jẹ onígbàgbọ òdodo. | ti eyin ba je onigbagbo ododo. |
Nígbà tá a ń padà bọ̀ sílé míṣọ́nnárì láti wá jẹ oúnjẹ ọ̀sán , Ben àti Karen ṣàlàyé pé àwọn ní láti wéwèé bí àwọn ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì dáadáa , nítorí pé àwọn lè lọ bẹ̀rẹ̀ àwọn ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tó pọ̀ ju èyí táwọn máa lè darí lọ . | Nigba ta a n pada bo sile misonnari lati wa je ounje osan , Ben ati Karen salaye pe awon ni lati wewee bi awon se n se ikekoo Bibeli daadaa , nitori pe awon le lo bere awon ikekoo Bibeli to po ju eyi tawon maa le dari lo . |
Àǹfààní tó ní pọ̀ , nítorí Jẹ́nẹ́sísì jẹ́ ká mọ̀ pé gbogbo ènìyàn — láìka àwọ̀ ara wọn , ẹ̀yà wọn , tàbí orílẹ̀ - èdè tí wọ́n ti wá sí — gbogbo wọn ṣẹ̀ látọ̀dọ̀ àwọn òbí kan , ìwé yẹn tipa bẹ́ẹ̀ mú ìpìlẹ̀ èyíkéyìí tó lè wà fún ẹ̀tanú ẹ̀yà ìran kúrò . — Ìṣe 17 : 26 . | Anfaani to ni po , nitori Jenesisi je ka mo pe gbogbo eniyan -- laika awo ara won , eya won , tabi orile - ede ti won ti wa si -- gbogbo won se latodo awon obi kan , iwe yen tipa bee mu ipile eyikeyii to le wa fun etanu eya iran kuro . -- Ise 17 : 26 . |
Àṣẹ tó pa fáwọn tó nífẹ̀ẹ́ ìdájọ́ òdodo àti òdodo ni : “ Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀ , [ ìyẹn Bábílónì Ńlá , ilẹ̀ ọba ìsìn èké àgbáyé ] , ẹ̀yin ènìyàn mi , bí ẹ kò bá fẹ́ ṣàjọpín pẹ̀lú rẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ , bí ẹ kò bá sì fẹ́ gbà lára àwọn ìyọnu àjàkálẹ̀ rẹ̀ . | Ase to pa fawon to nifee idajo ododo ati ododo ni : “ E jade kuro ninu re , [ iyen Babiloni Nla , ile oba isin eke agbaye ] , eyin eniyan mi , bi e ko ba fe sajopin pelu re ninu awon ese re , bi e ko ba si fe gba lara awon iyonu ajakale re . |
ẹ) Oun kò lè şe é. | e) Oun ko le se e. |
Èyí máa gba pé ká máa kíyè sí bí wọ́n ṣe ń tẹ̀ síwájú nínú ìjọ . | Eyi maa gba pe ka maa kiye si bi won se n te siwaju ninu ijo . |
Bó ṣe mọ Jèhófà Ọlọ́run tó sì wá nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ nìyẹn o . | Bo se mo Jehofa Olorun to si wa nifee re niyen o . |
Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá tí Karla fi ń bá mi lọ káàkiri nínú iṣẹ́ àyíká , ó wá di dandan kí wọ́n ṣe iṣẹ́ abẹ fún un . | Leyin odun mewaa ti Karla fi n ba mi lo kaakiri ninu ise ayika , o wa di dandan ki won se ise abe fun un . |
“Máa jẹ́ ǹṣó” lọ̀yà fi ńju ẹmọ́ lọ. | "Maa je nso" loya fi nju emo lo. |
Ẹ ti ya ara yín kúrò lọ́dọ̀ Kristi, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fẹ́ ìdáláre nípa òfin. Ẹ ti yapa kúrò ní ọ̀nà oore-ọ̀fẹ́. | E ti ya ara yin kuro lodo Kristi, eyin ti e n fe idalare nipa ofin. E ti yapa kuro ni ona oore-ofe. |
“ Ìwọ ti rọra fi ohun wọ̀nyí pa mọ́ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n àti amòye , o sì ti ṣí wọn payá fún àwọn ìkókó . ” — LÚÙKÙ 10 : 21 . | “ Iwo ti rora fi ohun wonyi pa mo kuro lodo awon ologbon ati amoye , o si ti si won paya fun awon ikoko . ” — LUUKU 10 : 21 . |
Ẹ JẸ́ KÍ ÌGBÀGBỌ́ YÍN LÁGBÁRA | E JE KI IGBAGBO YIN LAGBARA |
Ohun tó ran Capito , Cellarius , Campanus àti àwọn míì lọ́wọ́ láti mọ ìyàtọ̀ láàárìn òtítọ́ àti èké ni pé wọ́n fara balẹ̀ kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tọkàntọkàn . | Ohun to ran Capito , Cellarius , Campanus ati awon mii lowo lati mo iyato laaarin otito ati eke ni pe won fara bale kekoo Bibeli tokantokan . |
I asked the branch office if we could serve where there was a greater need for publishers , so they asked us to go to Nördlingen , Bavaria . | I asked the branch office if we could serve where there was a greater need for publishers , so they asked us to go to Nordlingen , Bavaria . |
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 29 ] | [ Aworan to wa ni oju iwe 29 ] |
Wọ́n ti fi ba ara wọn jẹ́ . | Won ti fi ba ara won je . |
Àmọ́ mi ò tètè tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ Bíbélì tí mò ń kọ́ torí iṣẹ́ mi àti irú ìgbé ayé tí mo ń gbé kì í jẹ́ kí n ráyè . | Amo mi o tete te siwaju ninu eko Bibeli ti mo n ko tori ise mi ati iru igbe aye ti mo n gbe ki i je ki n raye . |
Gbọ́ ariwo lórí òkè, bí ohùn ọ̀pọ̀ eniyan,gbọ́ ariwo ìdàrúdàpọ̀ ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ń péjọ pọ̀!OLUWA àwọn ọmọ ogunní ń kó àwọn ọmọ ogun jọ fún ogun. | Gbo ariwo lori oke, bi ohun opo eniyan,gbo ariwo idarudapo ijoba awon orile-ede ti o n pejo po!OLUWA awon omo ogunni n ko awon omo ogun jo fun ogun. |
A gbọ́ pé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lórílẹ̀ - èdè Jámánì ń fojú winá inúnibíni , a sì mọ̀ pé kò ní pẹ́ dé ọ̀dọ́ wa . | A gbo pe awon Elerii Jehofa to wa lorile - ede Jamani n foju wina inunibini , a si mo pe ko ni pe de odo wa . |
Bí Jésù ṣe fínnúfíndọ̀ ṣe iṣẹ́ ìyanu yìí mú kó dá wa lójú pé òun àti Baba rẹ̀ kò fọwọ́ kékeré mú bí nǹkan ṣe ń rí lára àwọn èèyàn . | Bi Jesu se finnufindo se ise iyanu yii mu ko da wa loju pe oun ati Baba re ko fowo kekere mu bi nnkan se n ri lara awon eeyan . |
Ka Ìṣe 8 : 35 , 36 . | Ka Ise 8 : 35 , 36 . |
Gẹ́gẹ́ bí ẹnì kan tó ti gbéyàwó , Jóòbù kì í wo àwọn ọ̀dọ́bìnrin ní ìwòkuwò , bẹ́ẹ̀ náà ni kì í gbèrò àtiṣe panṣágà nínú ọkàn - àyà rẹ̀ . | Gege bi eni kan to ti gbeyawo , Joobu ki i wo awon odobinrin ni iwokuwo , bee naa ni ki i gbero atise pansaga ninu okan - aya re . |
Lóde òní , ọ̀pọ̀ Ẹlẹ́rìí ni kì í lọ́wọ́ sí ọ̀rọ̀ òṣèlú tàbí ogun . | Lode oni , opo Elerii ni ki i lowo si oro oselu tabi ogun . |
Lẹ́yìn tí mo tẹ̀wọ̀n dé , wọ́n ní kí n máa bójú tó oko tá a ti ń pèsè nǹkan jíjẹ fún ìdílé Bẹ́tẹ́lì . | Leyin ti mo tewon de , won ni ki n maa boju to oko ta a ti n pese nnkan jije fun idile Beteli . |
lati ṣe àwáwí kankan. | lati se awawi kankan. |
Jónátanì sì bọ́ aṣọ ìgúnwà, ó sì fi fun Dáfídì pẹ̀lú aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ àti pẹ̀lú idà rẹ̀, ọrun rẹ̀ àti àmùrè rẹ̀ | Jonatani si bo aso igunwa, o si fi fun Dafidi pelu aso awotele re ati pelu ida re, orun re ati amure re |
tí wọn n sọ, kí ô sì rántí ẹrúsìn Wa | ti won n so, ki o si ranti erusin Wa |
Àbí ẹni tí Ọlọ́run ti kọ̀ ni ? | Abi eni ti Olorun ti ko ni ? |
sáánánì | saanani |
Àmì ẹ̀yẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards (AMVCA 2014) gẹ̀gẹ̀ bi amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tí ó dára jùlọ fún ipa rẹ̀ nínu fíìmù Flower Girl.[1] Àmì ẹ̀yẹ ti Nollywood Movies Awards (NMA 2014)[2] Àmì ẹ̀yẹ ti Nigeria Entertainment Awards (NEA 2014)[3] Àmì ẹ̀yẹ ti National Association of Nigerian Theatre Arts Practitioners (NANTAP) | Ami eye ti Africa Magic Viewers Choice Awards (AMVCA 2014) gege bi amugbalegbee oserebinrin ti o dara julo fun ipa re ninu fiimu Flower Girl.[1] Ami eye ti Nollywood Movies Awards (NMA 2014)[2] Ami eye ti Nigeria Entertainment Awards (NEA 2014)[3] Ami eye ti National Association of Nigerian Theatre Arts Practitioners (NANTAP) |
Ní August 1997 , ọwọ́ wa tẹ ohun kan tá a ti ń fojú sọ́nà fún . | Ni August 1997 , owo wa te ohun kan ta a ti n foju sona fun . |
Dáfídì sọ pé : “ Ìwọ tìkára rẹ ni ó ṣe àwọn kíndìnrín mi ; ìwọ ni ó yà mí sọ́tọ̀ nínú ikùn ìyá mi . ” | Dafidi so pe : “ Iwo tikara re ni o se awon kindinrin mi ; iwo ni o ya mi soto ninu ikun iya mi . ” |
Lẹ́yìn tí mo gbàdúrà fún okun , mo kan ilẹ̀kùn tí mo máa kọ́kọ́ kàn pàá láti wàásù . | Leyin ti mo gbadura fun okun , mo kan ilekun ti mo maa koko kan paa lati waasu . |
Ka Mátíù 13 : 47 - 50 . | Ka Matiu 13 : 47 - 50 . |
Àmọ́ alàgbà kan bá a sọ̀rọ̀ , ó sì rán an létí àwọn ìgbà tó ti ń fi ìṣòtítọ́ sìn , èyí wá mú kó tún inú rò . | Amo alagba kan ba a soro , o si ran an leti awon igba to ti n fi isotito sin , eyi wa mu ko tun inu ro . |
Ìjà wọ̀nyí níbi ìsìnkú sì wé mọ́ ọ̀ràn òṣèlú . . . nítorí pé àwọn aráàlú tí ń dìbò nífẹ̀ẹ́ àtimáa wo ìjà wọ̀nyẹn . | Ija wonyi nibi isinku si we mo oran oselu . . . nitori pe awon araalu ti n dibo nifee atimaa wo ija wonyen . |
O lè gbẹ́kẹ̀ lé àwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì látòkèdélẹ̀ nítorí ọ̀dọ̀ “ Jèhófà Ọlọ́run òtítọ́ ” ni wọ́n ti wá . — Sáàmù 31 : 5 . | O le gbeke le awon ileri to wa ninu Bibeli latokedele nitori odo “ Jehofa Olorun otito ” ni won ti wa . — Saamu 31 : 5 . |
Nígbà náà, Jesu gbé àwọn ọmọ náà lé ọwọ́ rẹ̀, ó gbé ọwọ́ lé orí wọn. Ó sì súre fún wọn. | Nigba naa, Jesu gbe awon omo naa le owo re, o gbe owo le ori won. O si sure fun won. |
4 : 1 - 14 : Ìran yìí mú un dá àwọn Júù lójú pé àwọn ìṣòro tó dà bí òkè yóò di pẹ̀tẹ́lẹ̀ àti pé Gómìnà Serubábélì yóò parí kíkọ́ tẹ́ńpìlì náà . | 4 : 1 - 14 : Iran yii mu un da awon Juu loju pe awon isoro to da bi oke yoo di petele ati pe Gomina Serubabeli yoo pari kiko tenpili naa . |
Àṣẹ yìí ni mo pa fun yín: ẹ fẹ́ràn ara yín.Ṣugbọn ọlọ́rọ̀ náà ní, ‘Ó tì, Abrahamu, Baba! Bí ẹnìkan bá jí dìde ninu òkú, tí ó lọ sọ́dọ̀ wọn, wọn yóo ronupiwada.’ Mose ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un. Ó mú Joṣua wá siwaju Eleasari alufaa ati gbogbo àwọn eniyan, Kí ló dé tí OLUWA fi ń mú wa lọ sí ilẹ̀ náà kí àwọn ọ̀tá wa lè pa wá, kí wọ́n sì kó àwọn aya ati àwọn ọmọ wa lẹ́rú. Ǹjẹ́ kò ní sàn fún wa kí á pada sí Ijipti?” “Báyìí tún ni ìjọba ọ̀run rí. Ó dàbí ọkunrin oníṣòwò kan tí ó ń wá ìlẹ̀kẹ̀ olówó iyebíye kan. Jedaaya ọmọ Harumafi ló ṣe àtúnṣe abala tí ó tẹ̀lé tiwọn, ó tún apá ibi tí ó kọjú sí ilé rẹ̀ ṣe.Lẹ́yìn wọn, Hatuṣi ọmọ Haṣabineya ṣe àtúnṣe tiwọn.Ìlú Ninefe dàbí adágún odòtí omi rẹ̀ ti ṣàn lọ.Wọ́n ń kígbe pé, “Ẹ dúró! Ẹ dúró!”Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó yíjú pada.Ṣugbọn lẹ́yìn tí a bá ti jí mi dìde, n óo ṣiwaju yín lọ sí Galili.” Oluwa wá sọ fún un pé, “Ẹ̀yin Farisi a máa fọ òde kọ́ọ̀bù ati àwo oúnjẹ, ṣugbọn inú yín kún fún ìwà ipá ati nǹkan burúkú! Ṣugbọn Isaaki ni Abrahamu kó gbogbo ohun ìní rẹ̀ fún. Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, gbogbo àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbà ìlú jọ forí-korí nípa ọ̀ràn Jesu, kí wọ́n lè pa á. òun OLUWA óo fìyà jẹ Ṣemaaya ará Nehelamu náà ati ìran rẹ̀; kò ní sí ẹnikẹ́ni tí yóo wà láàyè láàrin àwọn eniyan rẹ̀ láti fojú rí nǹkan rere tí n óo ṣe fún àwọn eniyan mi, nítorí ó ti sọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀ sí OLUWA.”Nítorí ó jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí ó burú jù,ẹ̀ṣẹ̀ tí adájọ́ gbọdọ̀ jẹ mí níyà fún.Nítorí Ọmọ-Eniyan ni Oluwa Ọjọ́ Ìsinmi.”Báwo ní ẹ ṣe lè wí pé ẹ kì í ṣe aláìmọ́;ati pé ẹ kò tẹ̀lé àwọn oriṣa Baali?Ẹ wo irú ìwà tí ẹ hù ninu àfonífojì,kí ẹ ranti gbogbo ibi tí ẹ ṣebí ọmọ ràkúnmí tí ń lọ, tí ń bọ̀;tí ń tọ ipa ọ̀nà ara rẹ̀.Doegi, olórí darandaran Saulu, ará Edomu wà níbẹ̀ ní ọjọ́ náà, nítorí pé ó ń jọ́sìn níwájú OLUWA.Ìbànújẹ́ ni kí eniyan bí ọmọ tí kò gbọ́n,kò sí ayọ̀ fún baba òmùgọ̀.A fi ọwọ́ rọ́ ẹjọ́ ẹ̀tọ́ sẹ́yìn,òdodo sì takété.Òtítọ́ ti ṣubú ní gbangba ìdájọ́,ìdúróṣinṣin kò rọ́nà wọlé.Bí mo bá tìtorí iyì eniyan bá ẹranko jà ní Efesu, anfaani wo ni ó ṣe fún mi? Bí a kò bá jí àwọn òkú dìde, bí wọ́n ti máa ń wí, wọn á ní:“Ẹ jẹ́ kí á máa jẹ, kí á máa mu,nítorí ọ̀la ni a óo kú.”Peteru bá ti gbogbo wọn jáde, ó kúnlẹ̀, ó gbadura. Ó bá kọjú sí òkú náà, ó ní, “Tabita, dìde.” Ni Tabita bá lajú, ó rí Peteru, ó bá dìde jókòó. Ìpa à ńpoṣè ara ló fi ńsan. | Ase yii ni mo pa fun yin: e feran ara yin.Sugbon oloro naa ni, ‘O ti, Abrahamu, Baba! Bi enikan ba ji dide ninu oku, ti o lo sodo won, won yoo ronupiwada.’ Mose se gbogbo ohun ti OLUWA pa lase fun un. O mu Josua wa siwaju Eleasari alufaa ati gbogbo awon eniyan, Ki lo de ti OLUWA fi n mu wa lo si ile naa ki awon ota wa le pa wa, ki won si ko awon aya ati awon omo wa leru. Nje ko ni san fun wa ki a pada si Ijipti?” “Bayii tun ni ijoba orun ri. O dabi okunrin onisowo kan ti o n wa ileke olowo iyebiye kan. Jedaaya omo Harumafi lo se atunse abala ti o tele tiwon, o tun apa ibi ti o koju si ile re se.Leyin won, Hatusi omo Hasabineya se atunse tiwon.Ilu Ninefe dabi adagun odoti omi re ti san lo.Won n kigbe pe, “E duro! E duro!”Sugbon ko si eni ti o yiju pada.Sugbon leyin ti a ba ti ji mi dide, n oo siwaju yin lo si Galili.” Oluwa wa so fun un pe, “Eyin Farisi a maa fo ode koobu ati awo ounje, sugbon inu yin kun fun iwa ipa ati nnkan buruku! Sugbon Isaaki ni Abrahamu ko gbogbo ohun ini re fun. Nigba ti ile mo, gbogbo awon olori alufaa ati awon agba ilu jo fori-kori nipa oran Jesu, ki won le pa a. oun OLUWA oo fiya je Semaaya ara Nehelamu naa ati iran re; ko ni si enikeni ti yoo wa laaye laarin awon eniyan re lati foju ri nnkan rere ti n oo se fun awon eniyan mi, nitori o ti soro ote si OLUWA.”Nitori o je ese ti o buru ju,ese ti adajo gbodo je mi niya fun.Nitori Omo-Eniyan ni Oluwa Ojo Isinmi.”Bawo ni e se le wi pe e ki i se alaimo;ati pe e ko tele awon orisa Baali?E wo iru iwa ti e hu ninu afonifoji,ki e ranti gbogbo ibi ti e sebi omo rakunmi ti n lo, ti n bo;ti n to ipa ona ara re.Doegi, olori darandaran Saulu, ara Edomu wa nibe ni ojo naa, nitori pe o n josin niwaju OLUWA.Ibanuje ni ki eniyan bi omo ti ko gbon,ko si ayo fun baba omugo.A fi owo ro ejo eto seyin,ododo si takete.Otito ti subu ni gbangba idajo,idurosinsin ko rona wole.Bi mo ba titori iyi eniyan ba eranko ja ni Efesu, anfaani wo ni o se fun mi? Bi a ko ba ji awon oku dide, bi won ti maa n wi, won a ni:“E je ki a maa je, ki a maa mu,nitori ola ni a oo ku.”Peteru ba ti gbogbo won jade, o kunle, o gbadura. O ba koju si oku naa, o ni, “Tabita, dide.” Ni Tabita ba laju, o ri Peteru, o ba dide jokoo. Ipa a npose ara lo fi nsan. |
Àmọ́ ṣá o , awòràwọ̀ làwọn àlejò yìí . | Amo sa o , aworawo lawon alejo yii . |
Nígbà tí gbogbo rẹ̀ kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ , àwọn òǹwòran ò fi bẹ́ẹ̀ rí ìyàtọ̀ kan dà bí alárà . | Nigba ti gbogbo re koko bere , awon onworan o fi bee ri iyato kan da bi alara . |
ẹni tí kì í ṣe Larubawa ni, | eni ti ki i se Larubawa ni, |
Inú Ọlọ́run máa ń dùn láti pèsè àwọn nǹkan wọ̀nyẹn fún wa . | Inu Olorun maa n dun lati pese awon nnkan wonyen fun wa . |
Torí náà , ìwé gbédègbẹ́yọ̀ The International Standard Bible Encyclopedia sọ pé : “ Kò tún yẹ ká máa ka ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ràkúnmí ní ìgbà àwọn baba ńlá sí àṣìṣe mọ́ níwọ̀n bí a ti rí ẹ̀rí tó pọ̀ tó látinú ohun tí àwọn awalẹ̀pìtàn hú jáde pé ṣáájú ìgbà àwọn baba ńlá ni wọ́n ti ń sin ràkúnmí . ” | Tori naa , iwe gbedegbeyo The International Standard Bible Encyclopedia so pe : " Ko tun ye ka maa ka ohun ti Bibeli so nipa awon rakunmi ni igba awon baba nla si asise mo niwon bi a ti ri eri to po to latinu ohun ti awon awalepitan hu jade pe saaju igba awon baba nla ni won ti n sin rakunmi . " |
Wọ́n máa ń pè é ní ìdámẹ́wàá , ìyẹn ni pé káwọn ọmọ ìjọ wọn fi ìdá kan nínú mẹ́wàá owó tó bá ń wọlé fún wọn ṣètọrẹ sí ṣọ́ọ̀ṣì . | Won maa n pe e ni idamewaa , iyen ni pe kawon omo ijo won fi ida kan ninu mewaa owo to ba n wole fun won setore si soosi . |
ati àwọn arakunrin wọn: Ṣebanaya ati Hodaya, Kelita, Pelaaya, ati Hanani, | ati awon arakunrin won: Sebanaya ati Hodaya, Kelita, Pelaaya, ati Hanani, |
Ó jẹ́ ọ̀kan nínu àwọn ọmọ obìnrin Ààrẹ orílẹ̀-èdè Sìmbábúè lọ́wọ́lọ́wọ́ ti orúkọ rẹ̀ n ṣe Emmerson Mnangagwa. | O je okan ninu awon omo obinrin Aare orile-ede Simbabue lowolowo ti oruko re n se Emmerson Mnangagwa. |
Oríṣiríṣi tíọ́rì ni ó wà bí i tíọ́rì ìfojú ààtò wo tíọ́rì ìfojú ìhun wo tíọ́rì ìfojú ìmọ̀ìbáraẹnígbépọ̀ láwùjọ wo tíọ́rì ìfojú àṣà ìbílẹ̀ wo tíọ́rì Ìṣègbèfábo tíọ́rì Soṣíọ́lọ́jì tí o tẹ̀lé ìlànà àti èrò tíọ́rì ìtàn ìgbésí ayé òǹkọ̀wé tíọ́rì Asàtakò Ìmúnisìn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ Ṣùgbọ́n nínú gbogbo àwọn tíọ́rì wọ̀nyí tíọ́rì tí o tẹ̀lé ìlànà àti èrò ni a máa ṣe àmúlò Àwọn agbátẹrù tíọ́rì yìí gbà pé ohun èlò tí àwùjọ lè fún ìjàgbara àwùjọ ní iṣẹ́ ọnà aláwòmọ́ lítíréṣọ̀ jẹ́ | Orisirisi tiori ni o wa bi i tiori ifoju aato wo tiori ifoju ihun wo tiori ifoju imoibaraenigbepo lawujo wo tiori ifoju asa ibile wo tiori Isegbefabo tiori Sosioloji ti o tele ilana ati ero tiori itan igbesi aye onkowe tiori Asatako Imunisin ati bee bee lo Sugbon ninu gbogbo awon tiori wonyi tiori ti o tele ilana ati ero ni a maa se amulo Awon agbateru tiori yii gba pe ohun elo ti awujo le fun ijagbara awujo ni ise ona alawomo litireso je |
Ṣé o lè fojú inú wo bó ṣe máa rí lára Tímótì nígbà tí Pọ́ọ̀lù fa iṣẹ́ yẹn lé e lọ́wọ́ ? | Se o le foju inu wo bo se maa ri lara Timoti nigba ti Poolu fa ise yen le e lowo ? |
'Àwa kì yòò ṣe àbòsí fún wọn bí tií | 'Awa ki yoo se abosi fun won bi tii |
Wọ́n ń fi àsìkò náà lọ wàásù láwọn ibi tó jẹ́ àdádó . | Won n fi asiko naa lo waasu lawon ibi to je adado . |
Ìlànà àkọ́kọ́ níbi àpérò náà kà pé : “ Àwọn ẹni ẹ̀mí tó dára ni Ọlọ́run fi èṣù àtàwọn ẹ̀mí èṣù yòókù dá níbẹ̀rẹ̀ , àmọ́ àwọn fúnra wọn ló sọra wọn di ẹ̀mí búburú . ” | Ilana akoko nibi apero naa ka pe : " Awon eni emi to dara ni Olorun fi esu atawon emi esu yooku da nibere , amo awon funra won lo sora won di emi buburu . " |
Ọba dá obinrin náà lóhùn pé, “Ọ̀rọ̀ kan ni mo fẹ́ bèèrè lọ́wọ́ rẹ, mo sì fẹ́ kí o sọ òtítọ́ rẹ̀ fún mi.”Obinrin náà dáhùn pé, “Kabiyesi, bèèrè ohunkohun tí o bá fẹ́.” | Oba da obinrin naa lohun pe, "Oro kan ni mo fe beere lowo re, mo si fe ki o so otito re fun mi."Obinrin naa dahun pe, "Kabiyesi, beere ohunkohun ti o ba fe." |
Ọ̀rọ̀ Hébérù tá a tú sí “ inú - rere - onífẹ̀ẹ́ ” tún túmọ̀ sí “ ìfẹ́ dídúróṣinṣin . ” | Oro Heberu ta a tu si " inu - rere - onifee " tun tumo si " ife didurosinsin . " |
Tá a bá jẹ́ kí ìbẹ̀rù Jèhófà jinlẹ̀ lọ́kàn àwọn ọmọ wa , ìpìlẹ̀ ẹ̀kọ́ tó máa jẹ́ kí wọ́n ní ògidì ọgbọ́n la fi lélẹ̀ yẹn . | Ta a ba je ki iberu Jehofa jinle lokan awon omo wa , ipile eko to maa je ki won ni ogidi ogbon la fi lele yen . |
Mo wá bẹ̀rẹ̀ sí kọ gbogbo ohun tí mo bá ti rántí sílẹ̀ , irú bí àwọn ẹsẹ Bíbélì , gbólóhùn látinú Ilé Ìṣọ́ , àtàwọn àyọkà látinú àwọn ìwé mìíràn tó jẹ́ ti Kristẹni . | Mo wa bere si ko gbogbo ohun ti mo ba ti ranti sile , iru bi awon ese Bibeli , gbolohun latinu Ile Iso , atawon ayoka latinu awon iwe miiran to je ti Kristeni . |
máa jó tùràrí lórí rẹ̀ | maa jo turari lori re |
Ẹlòmíì tún ni Lennart , ẹni ọdún márùndínlọ́gọ́rin [ 75 ] tó ń gbé ní Sweden , bó tiẹ̀ jẹ́ pé kò rọrùn fún un , ó kọ́ èdè tuntun . | Elomii tun ni Lennart , eni odun marundinlogorin [ 75 ] to n gbe ni Sweden , bo tie je pe ko rorun fun un , o ko ede tuntun . |
Àmọ́ , ọ̀kan lára àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ lọ ṣòfófó fún àwọn ọlọ́pàá , wọ́n sì mú oníṣòwò náà . | Amo , okan lara awon osise re lo sofofo fun awon olopaa , won si mu onisowo naa . |
Á bi ara rẹ̀ pé : ‘ Wọ́n ní ògùn tàbí egbòogi yìí ti wo ẹnì kan sàn , àmọ́ ṣé mo ti rí àwọn tí ògùn náà wò sàn lóòótọ́ ? | A bi ara re pe : ‘ Won ni ogun tabi egboogi yii ti wo eni kan san , amo se mo ti ri awon ti ogun naa wo san loooto ? |
Basluti, Mehida, Harṣa, | Basluti, Mehida, Harsa, |
Àwọn èèyàn Ọlọ́run lóde òní kì í ja ogun nípa tara , àmọ́ wọ́n ń dojú kọ ọ̀pọ̀ àdánwò àti ìpèníjà . | Awon eeyan Olorun lode oni ki i ja ogun nipa tara , amo won n doju ko opo adanwo ati ipenija . |
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ tètè dá àwọn ìwé àṣẹ ìṣojúfúnni , tí a ó fi ránṣẹ́ sí àwọn mẹ́ńbà pẹ̀lú ìfitónilétí nípa ìpàdé ọdọọdún náà padà , kí ó bàa lè dé Ọ́fíìsì Akọ̀wé Society , ó pẹ́ tán ní August 1 . | E jowo e tete da awon iwe ase isojufunni , ti a o fi ranse si awon menba pelu ifitonileti nipa ipade odoodun naa pada , ki o baa le de Ofiisi Akowe Society , o pe tan ni August 1 . |
Ọ̀rọ̀ ohun tó ṣẹlẹ̀ ní Édẹ́nì dà bí ìgbà tí ọkùnrin kan bá bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé sórí ilẹ̀ kan tó dáa . | Oro ohun to sele ni Edeni da bi igba ti okunrin kan ba bere si i ko ile sori ile kan to daa . |
Níwọ̀n bí Ẹlẹ́dàá wa , Jèhófà Ọlọ́run , ti wá ojútùú sí ìṣòro omi láwọn àkókò tó kọjá , ǹjẹ́ kò tún ní ṣe bẹ́ẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ? | Niwon bi Eledaa wa , Jehofa Olorun , ti wa ojutuu si isoro omi lawon akoko to koja , nje ko tun ni se bee lojo iwaju ? |
átẹ́nsì | atensi |
Mo ti di àlejò lọ́dọ̀ àwọn arakunrin mi,mo sì di àjèjì lọ́dọ̀ àwọn ọmọ ìyá mi. | Mo ti di alejo lodo awon arakunrin mi,mo si di ajeji lodo awon omo iya mi. |
Ó sọ pé , “ Kódà ní báyìí , mo ṣì máa ń sapá gan - an láti ṣẹ́pá ìbínú mi torí pé inú ilé tínú ti tètè máa ń bí àwọn èèyàn ni mo dàgbà sí . ” | O so pe , " Koda ni bayii , mo si maa n sapa gan - an lati sepa ibinu mi tori pe inu ile tinu ti tete maa n bi awon eeyan ni mo dagba si . " |
Nígbà tí Aṣojú-Olódùmarè fi máa dé púpọ̀ nínú àwọn aláìsàn ti kú, ara wọn kò lágbára láti gbé àìsàn tí wọ́n béèrè nígbà tí òun kọ́ wá. | Nigba ti Asoju-Olodumare fi maa de pupo ninu awon alaisan ti ku, ara won ko lagbara lati gbe aisan ti won beere nigba ti oun ko wa. |
Ìwé Kíkọ Ní Ísírẹ́lì Ayé Ọjọ́un , 8 / 15 | Iwe Kiko Ni Isireli Aye Ojoun , 8 / 15 |
Ṣé wọ́n gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ lọ gba àṣẹ ? ” | Se won gbodo koko lo gba ase ? " |
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé àpò àwọn ọ̀tọ̀kùlú ni èyí tó pọ̀ jù lọ nínú owó tó ń wọlé láti ọ̀dọ̀ àwọn oníṣòwò tó wà ní àgbègbè yìí àtèyí tí wọ́n ń rí láti inú àwọn nǹkan àmúṣọrọ̀ àgbègbè náà ń lọ dípò ọ̀dọ̀ àwọn gbáàtúù tí wọ́n ń ṣe èyí tó pọ̀ jù nínú iṣẹ́ náà . | O see se ko je pe apo awon otokulu ni eyi to po ju lo ninu owo to n wole lati odo awon onisowo to wa ni agbegbe yii ateyi ti won n ri lati inu awon nnkan amusoro agbegbe naa n lo dipo odo awon gbaatuu ti won n se eyi to po ju ninu ise naa . |
A ó lè fi han Ọlọ́run nísinsìnyí pé a ó lè fara mọ́ bí ìgbésí ayé á ṣe rí nínú ayé tuntun alálàáfíà tó ṣèlérí . | A o le fi han Olorun nisinsinyi pe a o le fara mo bi igbesi aye a se ri ninu aye tuntun alalaafia to seleri . |
Èmi àtàwọn àbúrò mi : ( iwájú , láti apá òsì sápá ọ̀tún ) Hannelore àti Sabine ; ( ẹ̀yìn , láti apá òsì sápá ọ̀tún ) èmi , Jochen , Peter , àti Manfred | Emi atawon aburo mi : ( iwaju , lati apa osi sapa otun ) Hannelore ati Sabine ; ( eyin , lati apa osi sapa otun ) emi , Jochen , Peter , ati Manfred |
Nítorí ohun tí Olúwa wí nìyìí | Nitori ohun ti Oluwa wi niyii |
Ní nǹkan bí oṣù márùn - ún lẹ́yìn náà , àwọn ọmọ ogun Róòmù ṣẹ́gun ìlú náà torí àwọn ará Jerúsálẹ́mù ò rí oúnjẹ jẹ mọ́ , wọ́n sì tún bẹ̀rẹ̀ sí í para wọn . | Ni nnkan bi osu marun - un leyin naa , awon omo ogun Roomu segun ilu naa tori awon ara Jerusalemu o ri ounje je mo , won si tun bere si i para won . |
SI. Lẹ̀hìn náà, àwọn kan yòò | SI. Lehin naa, awon kan yoo |
nìgbà | nigba |
bí ọ̀lẹ là á rí | bi ole la a ri |
Kódà , ìfẹ́ àrà ọ̀tọ̀ làwọn ará máa ń fi hàn sírú àwọn bẹ́ẹ̀ , bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tọ́rọ̀ kàn lè má tètè kíyè sí i . | Koda , ife ara oto lawon ara maa n fi han siru awon bee , bo tile je pe awon toro kan le ma tete kiye si i . |
Nígbà tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà bá ti ṣe ìpinnu kan tó bá Ìwé Mímọ́ mu , alàgbà kọ̀ọ̀kan yóò tẹ̀ lé ìdarí ẹ̀mí mímọ́ nípa títi ìpinnu yẹn lẹ́yìn àní bí ọ̀pọ̀ jù lọ kò tiẹ̀ tẹ́wọ́ gba èrò tirẹ̀ . | Nigba ti igbimo awon alagba ba ti se ipinnu kan to ba Iwe Mimo mu , alagba kookan yoo te le idari emi mimo nipa titi ipinnu yen leyin ani bi opo ju lo ko tie tewo gba ero tire . |
Wọ́n sì gòkè lọ sí ilẹ̀ òkè náà, wọ́n sì wá sí pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ésíkónì, wọ́n sì yẹ̀ ẹ́ wò | Won si goke lo si ile oke naa, won si wa si petele Esikoni, won si ye e wo |
Oníṣòwò mélòó ló lè pàdánù adúrú owó yẹn láìní kógbá sílé ? | Onisowo meloo lo le padanu aduru owo yen laini kogba sile ? |
ohun tí a ti fihàn sí àwọn ọmọ ènìyàn ni a ó fihàn ní ọjọ́ nã; Sátánì kì yíò sì ní agbára lórí ọkàn àwọn ọmọ ènìyàn mọ́, fún ìgbà pípẹ́. Àti nísisìyí, ẹ̀yin arákùnrin mi àyànfẹ́, mo fi òpin sí àwọn ọ̀rọ̀ sísọ mi. | ohun ti a ti fihan si awon omo eniyan ni a o fihan ni ojo na; Satani ki yio si ni agbara lori okan awon omo eniyan mo, fun igba pipe. Ati nisisiyi, eyin arakunrin mi ayanfe, mo fi opin si awon oro siso mi. |
Fífi Oyin Se Oúnjẹ | Fifi Oyin Se Ounje |