diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ibikíbi tí ẹ̀mí bá ń lọ, kẹ̀kẹ́ wọn yóò sì bá wọn lọ, nítorí pé ẹ̀mí àwọn ẹ̀dá alààyè yìí wà nínú kẹ̀kẹ́ wọn.
Ibikibi ti emi ba n lo, keke won yoo si ba won lo, nitori pe emi awon eda alaaye yii wa ninu keke won.
Ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà , àwọn èèyàn kan nílẹ̀ Yúróòpù àti láwọn ilẹ̀ míì bẹ̀rẹ̀ sí í túmọ̀ Bíbélì sáwọn èdè míì , wọ́n sì ń pín in fáwọn tó nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run .
Opo odun leyin naa , awon eeyan kan nile Yuroopu ati lawon ile mii bere si i tumo Bibeli sawon ede mii , won si n pin in fawon to nifee Oro Olorun .
Olúkúlùkù wa gbọdọ̀ máa ṣe ohun tí ó wu ọmọnìkejì rẹ̀ sí rere, láti gbé e ró.
Olukuluku wa gbodo maa se ohun ti o wu omonikeji re si rere, lati gbe e ro.
Kò ní bọ́gbọ́n mu kó o ronú pé o lè jẹ̀gbádùn díẹ̀ lára ohun tí kò dára láìrú òfin Ọlọ́run ní ti gidi , bíi pé o lè “ tọ́ ” ẹ̀ṣẹ̀ “ wò ” láìgbé e mì .
Ko ni bogbon mu ko o ronu pe o le jegbadun die lara ohun ti ko dara lairu ofin Olorun ni ti gidi , bii pe o le “ to ” ese “ wo ” laigbe e mi .
Bẹ̀rù Olúwa Ọlọ́run rẹ, Òun nìkan ni kí o sì máa sìn, búra ní orúkọ rẹ̀ nìkan
Beru Oluwa Olorun re, Oun nikan ni ki o si maa sin, bura ni oruko re nikan
Síbẹ̀ , ẹni yìí làwọn àpọ́sítélì adárarégèé ní Kọ́ríńtì sọ pé ọ̀rọ̀ rẹ̀ kò ní láárí !
Sibe , eni yii lawon apositeli adararegee ni Korinti so pe oro re ko ni laari !
Torí pé àwọn míì pààyàn ni wọ́n sì ṣe jù wọ́n sẹ́wọ̀n .
Tori pe awon mii paayan ni won si se ju won sewon .
Gbọ́ ti wa, Ọlọ́run wa, nítorí àwa di ẹni ẹ̀gàn. Dá ẹ̀gàn wọn padà sórí ara wọn. Kí o sì fi wọ́n fún ìkógun ní ilẹ̀ ìgbèkùn.
Gbo ti wa, Olorun wa, nitori awa di eni egan. Da egan won pada sori ara won. Ki o si fi won fun ikogun ni ile igbekun.
ẹkẹdógun
ekedogun
Àjọ yìí tún sọ pé kí ilé iṣẹ́ ìpẹ̀jọ́ ti ìjọba ṣèwádìí nípa ìgbòkègbodò ìsìn ti ọ̀gbẹ́ni Lyova Margaryan , Kristẹni alàgbà àti ògbóǹkangí amòfin tí ilé iṣẹ́ iná mànàmáná ìlú tó ń lo agbára átọ́míìkì gbà síṣẹ́ .
Ajo yii tun so pe ki ile ise ipejo ti ijoba sewadii nipa igbokegbodo isin ti ogbeni Lyova Margaryan , Kristeni alagba ati ogbonkangi amofin ti ile ise ina manamana ilu to n lo agbara atomiiki gba sise .
Kí ni ẹ̀gún tó wà nínú ẹran ara Pọ́ọ̀lù yìí ?
Ki ni egun to wa ninu eran ara Poolu yii ?
Àwọn oògùn tuntun tó dá lórí apilẹ̀ àbùdá tí wọ́n ṣe lọ́nà táá fi bá ohun tó ń ṣe oníkálùkù mu á ti wà fáwọn àìsàn bí àtọ̀gbẹ , àrùn ọkàn , àrùn Alzheimer tí kì í jẹ́ kí ọpọlọ ṣiṣẹ́ dáadáa , àrùn ọpọlọ dídàrú , àtàwọn àìlera míì tó ń gbẹ̀mí àwọn èèyàn láwùjọ wa . ”
Awon oogun tuntun to da lori apile abuda ti won se lona taa fi ba ohun to n se onikaluku mu a ti wa fawon aisan bi atogbe , arun okan , arun Alzheimer ti ki i je ki opolo sise daadaa , arun opolo didaru , atawon ailera mii to n gbemi awon eeyan lawujo wa . "
Káúdà ni wọ́n ń pe erékùṣù Gáfúdò nígbà yẹn .
Kauda ni won n pe erekusu Gafudo nigba yen .
Síbẹ̀ , àkókò ń bọ̀ tí a óò gbé ìjọsìn tòótọ́ ga lẹ́ẹ̀kan sí i .
Sibe , akoko n bo ti a oo gbe ijosin tooto ga leekan si i .
Máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn àgùntàn mi kéékèèké . . . .
Maa se oluso aguntan awon aguntan mi keekeeke . . . .
“Nígbà náà ni ọkùnrin tí ó jẹ́ alábojútó ilẹ̀ náà wí fún wa pé, ‘Báyìí ni n ó ṣe mọ̀ bóyá olóòtítọ́ ènìyàn ni yín; Ẹ fi ọ̀kan nínú àwọn arákùnrin yín sílẹ̀ níbí, pẹ̀lú mi, ẹ sì mú oúnjẹ lọ fún àwọn ará ilé yín tí ebi ń pa kú lọ, lọ́wọ́ ìyàn.
"Nigba naa ni okunrin ti o je alabojuto ile naa wi fun wa pe, 'Bayii ni n o se mo boya olootito eniyan ni yin; E fi okan ninu awon arakunrin yin sile nibi, pelu mi, e si mu ounje lo fun awon ara ile yin ti ebi n pa ku lo, lowo iyan.
Ẹ̀ka ọ́fíìsì àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní orílẹ̀ - èdè Austria fi bí ipò nǹkan ṣe rí tó àwọn ìjọ tó wà ní àdúgbò náà létí , wọ́n sì ṣètò owó àkànlò láti fi ṣèrànwọ́ .
Eka ofiisi awon Elerii Jehofa to wa ni orile - ede Austria fi bi ipo nnkan se ri to awon ijo to wa ni adugbo naa leti , won si seto owo akanlo lati fi seranwo .
“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọ́n yan àwọn ìlú ààbò tí mo bá Mose sọ nípa rẹ̀, pé kí ó sọ fun yín.
"So fun awon omo Israeli pe ki won yan awon ilu aabo ti mo ba Mose so nipa re, pe ki o so fun yin.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé oúnjẹ díẹ̀ ni Jeremáyà àti Èlíjà rí jẹ , síbẹ̀ Jèhófà bójú tó wọn .
Bo tile je pe ounje die ni Jeremaya ati Elija ri je , sibe Jehofa boju to won .
Lábẹ́ kinní bí awọsanma yìí ni àwọn ìyẹ́ wọn ti nà jáde, wọ́n kan ara wọn, àwọn ẹ̀dá alààyè náà ní ìyẹ́ meji meji tí wọ́n fi bora.
Labe kinni bi awosanma yii ni awon iye won ti na jade, won kan ara won, awon eda alaaye naa ni iye meji meji ti won fi bora.
àdéhùn wọn títí dôjú ikú; bẹ̀ẹ̀ni
adehun won titi doju iku; beeni
Èyí mú ká parí gbogbo ìpínlẹ̀ ìwàásù náà láàárín nǹkan bí ọgbọ̀n [ 30 ] ìṣẹ́jú .
Eyi mu ka pari gbogbo ipinle iwaasu naa laaarin nnkan bi ogbon [ 30 ] iseju .
  Òun sì yí gbogbo àwọn ọkùnrin Júdà lọ́kàn padà àní bí ọkàn ènìyàn kan
  Oun si yi gbogbo awon okunrin Juda lokan pada ani bi okan eniyan kan
Bí Law ṣe bẹ̀rẹ̀ sí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì nìyẹn , kò sì pẹ́ tó fí ń wá sípàdé .
Bi Law se bere si kekoo Bibeli niyen , ko si pe to fi n wa sipade .
Ọ̀rọ̀, ọ̀tún wẹ òsì, òsì wẹ ọ̀tún, lọwọ́ fi nmọ wúlò lati gba àwọn ènìà níyànjú wípé àgbájọwọ́ láàarín ẹbí, ọ̀rẹ́ àti ará ìlú lérè
Oro, otun we osi, osi we otun, lowo fi nmo wulo lati gba awon enia niyanju wipe agbajowo laaarin ebi, ore ati ara ilu lere
Nígbà tí Jeremiah wà nínú túbú, ọ̀rọ̀ tọ̀ ọ́ wá wí pé:
Nigba ti Jeremiah wa ninu tubu, oro to o wa wi pe:
Igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rẹ̀ jẹ́ déédé, gígùn rẹ̀ jẹ ìdajì mítà, fífẹ̀ rẹ̀ náà jẹ́ ìdajì mítà àti gíga rẹ̀ sì jẹ́ mítà kan-ìwo rẹ̀ sì jẹ́ bákan náà
Igun mereerin re je deede, gigun re je idaji mita, fife re naa je idaji mita ati giga re si je mita kan-iwo re si je bakan naa
ohun tí A ṣe ní ìlérí fún wọn hàn
ohun ti A se ni ileri fun won han
Báwo ni ìgbàgbọ́ wa ṣe lè lágbára gan - an ?
Bawo ni igbagbo wa se le lagbara gan - an ?
ẹ̀rù wọn ba òun ati àwọn eniyan rẹ̀ lọpọlọpọ, nítorí pé wọ́n pọ̀. Jìnnìjìnnì bo gbogbo àwọn ará Moabu nítorí àwọn ọmọ Israẹli.
eru won ba oun ati awon eniyan re lopolopo, nitori pe won po. Jinnijinni bo gbogbo awon ara Moabu nitori awon omo Israeli.
Èyí ya dókítà náà lẹ́nu .
Eyi ya dokita naa lenu .
Ìparun àwọn ẹni rírẹlẹ̀ ni ipò òṣì wọn . ”
Iparun awon eni rirele ni ipo osi won . ”
fún Un, òyí ni ọnà tí Òô tQ tààrà."
fun Un, oyi ni ona ti Oo tQ taara."
Ẹ wo bí Jésù ṣe rọra la ojú àwọn ọkùnrin méjì tó jẹ́ afọ́jú .
E wo bi Jesu se rora la oju awon okunrin meji to je afoju .
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Awon Ohun To Wa Ninu Iwe Yii
Lóòótọ́ , Ádámù àti Éfà ló jọ dẹ́ṣẹ̀ , àmọ́ Ádámù ni Ọlọ́run dá lẹ́bi .
Loooto , Adamu ati Efa lo jo dese , amo Adamu ni Olorun da lebi .
Àwọn kan sọ pé ohun tí ọ̀rẹ́ rẹ ṣe kò dáa , wọ́n sì dá a lẹ́bi pé ìkà ni .
Awon kan so pe ohun ti ore re se ko daa , won si da a lebi pe ika ni .
Ṣùgbọ́n , ọ̀ṣọ́ọ́rọ́ obìnrin kan , tó jẹ́ akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi ló ń ràn án lọ́wọ́ , tó ń fi ọmọlanke tì í kiri .
Sugbon , osooro obinrin kan , to je akede ti ko tii seribomi lo n ran an lowo , to n fi omolanke ti i kiri .
Àwọn ìlú tí ó wà ní ilẹ̀ náà ni: Jẹriko, Beti Hogila, Emeki Kesisi;
Awon ilu ti o wa ni ile naa ni: Jeriko, Beti Hogila, Emeki Kesisi;
Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu;
Lati odo Juda, Nahisoni omo Amminadabu;
Ìyẹn máa ń jẹ́ kí n mọ bí mo ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́ .
Iyen maa n je ki n mo bi mo se le ran won lowo .
Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo wọ́n jẹ́ ìran mẹ́rìnlá láti orí Abrahamu dé orí Dafidi, ìran mẹ́rìnlá á láti orí Dafidi títí dé ìkólọ sí Babeli, àti ìran mẹ́rìnlá láti ìkólọ títí dé orí Kristi.
Bee ni gbogbo won je iran merinla lati ori Abrahamu de ori Dafidi, iran merinla a lati ori Dafidi titi de ikolo si Babeli, ati iran merinla lati ikolo titi de ori Kristi.
ni, Emi ìbá tí le kà á fún yín, Òun
ni, Emi iba ti le ka a fun yin, Oun
Ṣé òótọ́ ni pé kò yẹ kó o mọ bó o ṣe lè máa tọ́jú ara rẹ ?
Se ooto ni pe ko ye ko o mo bo o se le maa toju ara re ?
Jona sì bẹ̀rẹ̀ sí wọ ìlú náà lọ ní ìrìn ọjọ́ kan, ó sì ń kéde, ó sì wí pé, “Níwọ́n ogójì ọjọ́ sí i, a ó bi Ninefe wó.”
Jona si bere si wo ilu naa lo ni irin ojo kan, o si n kede, o si wi pe, "Niwon ogoji ojo si i, a o bi Ninefe wo."
Bíbélì ṣe ìkìlọ̀ kan fáwọn lọ́kọláya .
Bibeli se ikilo kan fawon lokolaya .
Báwo lẹnì kan ṣe lè tẹ̀ lé ohun tí Ìwé Mímọ́ sọ yìí bí onítọ̀hún bá ń gbìyànjú láti sin Ọlọ́run lóun nìkan ?
Bawo leni kan se le te le ohun ti Iwe Mimo so yii bi onitohun ba n gbiyanju lati sin Olorun loun nikan ?
Ìrètí àgbàyanu mà lèyí o — àìsàn àti ọjọ́ ogbó kò ní sí mọ́ , wàá lè wà láàyè lọ láti gbádùn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ , wàá ní àlàáfíà pẹ̀lú àwọn ẹranko pàápàá !
Ireti agbayanu ma leyi o — aisan ati ojo ogbo ko ni si mo , waa le wa laaye lo lati gbadun ise owo re , waa ni alaafia pelu awon eranko paapaa !
Ó wí fún wọn pé, Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàni wọ̀nyí ṣe mí nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà níhìn-ín, kò sì sí ohun kan tí ó kù sílẹ̀ fún wọn láti jẹ
O wi fun won pe, Aanu opo eniyani wonyi se mi nitori pe o to ojo meta ti won ti wa nihin-in, ko si si ohun kan ti o ku sile fun won lati je
Síbẹ̀ , mo ṣì fẹ́ mọ̀ bóyá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣe ohun tí wọ́n ń wàásù rẹ̀ .
Sibe , mo si fe mo boya awon Elerii Jehofa maa n se ohun ti won n waasu re .
A sì tún ní láti gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà , nítorí a mọ̀ pé ó ń wá ire wa .
A si tun ni lati gbeke le Jehofa , nitori a mo pe o n wa ire wa .
Wọn ò nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ tó jẹ́ fún wọn , wọ́n sì tún kórìíra Ọlọ́run tó rán an níṣẹ́ .
Won o nifee si ise to je fun won , won si tun koriira Olorun to ran an nise .
Ó sì ṣe tí Nífáì kọjá lọ lãrín
O si se ti Nifai koja lo larin
Ṣé pé ìwà tèmi - yé - mi tàbí yíya ara ẹni láṣo ló ń yọ ẹni kan lẹ́nu tó bá sọ pé kìkì ẹni tí wọ́n jọ wà nínú ìsìn kan náà ni òún fẹ́ bá gbé ?
Se pe iwa temi - ye - mi tabi yiya ara eni laso lo n yo eni kan lenu to ba so pe kiki eni ti won jo wa ninu isin kan naa ni oun fe ba gbe ?
Mi ò mọ̀ nígbà yẹn pé mo ṣì máa láǹfààní láti dé ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀ - èdè yìí .
Mi o mo nigba yen pe mo si maa lanfaani lati de opo awon orile - ede yii .
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé akọrin kan ṣoṣo ló kọrin tẹ̀ lé e ( 91 : 9a ) , tí ẹgbẹ́ akọrin sì wá gberin ( 91 : 9b - 13 ) .
O see se ko je pe akorin kan soso lo korin te le e ( 91 : 9a ) , ti egbe akorin si wa gberin ( 91 : 9b - 13 ) .
Àjákù tí wọ́n rí nílùú Oxyrhynchus , ilẹ̀ Íjíbítì , tí wọ́n sì fún ní nọ́ńbà náà 3522 , ni wọ́n sọ pé ó ti wà láti ọ̀rúndún kìíní Sànmánì Tiwa .
Ajaku ti won ri niluu Oxyrhynchus , ile Ijibiti , ti won si fun ni nonba naa 3522 , ni won so pe o ti wa lati orundun kiini Sanmani Tiwa .
Ó sì jẹ́ ká mọ bí àdánwò ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní àwọn ànímọ́ tí kò ní jẹ́ kí àjọṣe àárín àwa àti Ọlọ́run bà jẹ́ . Àwọn ànímọ́ náà ni ìfaradà , ìgbàgbọ́ , àti ìwà títọ́ .
O si je ka mo bi adanwo se le ran wa lowo lati ni awon animo ti ko ni je ki ajose aarin awa ati Olorun ba je . Awon animo naa ni ifarada , igbagbo , ati iwa tito .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Bill àti Linda ń ràn mí lọ́wọ́ gan - an , síbẹ̀ mo ṣì ń ṣàyẹ̀wò àwọn ìsìn mìíràn .
Bo tile je pe Bill ati Linda n ran mi lowo gan - an , sibe mo si n sayewo awon isin miiran .
Jésù sọ fún Ọlọ́run pé : “ Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ . ” — Jòhánù 17 : 17 ; 2 Pétérù 1 : 20 , 21 .
Jesu so fun Olorun pe : “ Otito ni oro re . ” — Johanu 17 : 17 ; 2 Peteru 1 : 20 , 21 .
Kí oore-ọ̀fẹ́ ati alaafia láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun Baba wa ati Oluwa Jesu Kristi kí ó wà pẹlu yín.
Ki oore-ofe ati alaafia lati odo Olorun Baba wa ati Oluwa Jesu Kristi ki o wa pelu yin.
Èyí jẹ́ kí a lè ṣètò àwọn ìjọ wa sí àwọn àyíká .
Eyi je ki a le seto awon ijo wa si awon ayika .
àwọn olórí ìjọ ènìyàn sì wá, wọ́n sì sọ èyí fún Mósè
awon olori ijo eniyan si wa, won si so eyi fun Mose
Ẹ wo bí ìpinnu tó fìdí múlẹ̀ gbọn - in tí Jésù ṣe tọkàntọkàn ṣe yàtọ̀ sí àwáwí tí kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ tí àwọn ọkùnrin yẹn ṣe !
E wo bi ipinnu to fidi mule gbon - in ti Jesu se tokantokan se yato si awawi ti ko lese nile ti awon okunrin yen se !
ìjọ ogun tí ô parapọ náà ba tún padà
ijo ogun ti o parapo naa ba tun pada
Àkọ́kọ́ ni pé ọkàn rẹ̀ balẹ̀ pé Jèhófà yóò dá sí ọ̀rọ̀ náà , ekèjì sì ni pé ó ń ṣọ́nà .
Akoko ni pe okan re bale pe Jehofa yoo da si oro naa , ekeji si ni pe o n sona .
Ṣé àwọn ọkùnrin Rẹ̀ kò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ láti wá kiri àti samí sita orílẹ̀ èdè àti láti bì í ṣubú
Se awon okunrin Re ko wa si odo re lati wa kiri ati sami sita orile ede ati lati bi i subu
Ká sòótọ́ , irọ́ funfun báláú làwọn tó ń gbé àwòrán oníhòòhò jáde ń pa tí wọ́n bá sọ pé ó dáa kéèyàn máa wò ó .
Ka sooto , iro funfun balau lawon to n gbe aworan onihooho jade n pa ti won ba so pe o daa keeyan maa wo o .
Nípasẹ̀ wòlíì Aísáyà tí òun àti Míkà jọ gbé ayé lákòókò kan náà , Jèhófà lo ìgbà tí kì í tàsé àti àgbàyanu àyípoyípo omi láti ṣàlàyé bí ọ̀rọ̀ rẹ̀ ti ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé tó .
Nipase wolii Aisaya ti oun ati Mika jo gbe aye lakooko kan naa , Jehofa lo igba ti ki i tase ati agbayanu ayipoyipo omi lati salaye bi oro re ti see gbeke le to .
Bẹ́ẹ̀ ni, Jehoramu lọ síbẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìjòyè rẹ̀ àti gbogbo àwọn kẹ̀kẹ́. Àwọn ará Edomu yí i ká àti àwọn alákòóso àwọn kẹ̀kẹ́ rẹ̀. Ṣùgbọ́n ó dìde ní òru ó sì ṣẹ́gun wọn ní òru.
Bee ni, Jehoramu lo sibe pelu awon ijoye re ati gbogbo awon keke. Awon ara Edomu yi i ka ati awon alakooso awon keke re. Sugbon o dide ni oru o si segun won ni oru.
Tún gbà á nímọ̀ràn pé kó pinnu láti ka Bíbélì látòkèdélẹ̀ .
Tun gba a nimoran pe ko pinnu lati ka Bibeli latokedele .
Lọ́nà yìí , ó yẹ kí àwọn ọkọ máa nífẹ̀ẹ́ àwọn aya wọn gẹ́gẹ́ bí ara àwọn fúnra wọn .
Lona yii , o ye ki awon oko maa nifee awon aya won gege bi ara awon funra won .
wọn kò ní dẹkun.
won ko ni dekun.
Mo fẹ́ ẹ́ fi dá a yín lójú pé , díẹ̀díẹ̀ ni ìfẹ́ láti wo ìṣekúṣe oníwà ipá yìí máa ń wọ èèyàn lára .
Mo fe e fi da a yin loju pe , diedie ni ife lati wo isekuse oniwa ipa yii maa n wo eeyan lara .
Kí ló máa jẹ́ káwọn àjíǹde tí àkọsílẹ̀ rẹ̀ wà nínú Bíbélì tù wá nínú ?
Ki lo maa je kawon ajinde ti akosile re wa ninu Bibeli tu wa ninu ?
Bó ṣe di pé mo ní láti lọ fẹnu ara mi ṣàlàyé fáwọn ará abúlé nìyẹn o .
Bo se di pe mo ni lati lo fenu ara mi salaye fawon ara abule niyen o .
Kálukú ló lómìnira láti ṣe ẹ̀sìn tó wù ú .
Kaluku lo lominira lati se esin to wu u .
Báwo ni ìdájọ́ náà ṣe máa wáyé ?
Bawo ni idajo naa se maa waye ?
Ẹni tó jókòó lórí ìtẹ́ náà dà bí “ òkúta jásípérì . ”
Eni to jokoo lori ite naa da bi " okuta jasiperi . "
Àwọn ẹran tí ẹ lè jẹ nìwọ̀nyí: mààlúù, aguntan,
Awon eran ti e le je niwonyi: maaluu, aguntan,
Kí Ísírẹ́lì máa bá a nìṣó ní dídúró de Jèhófà . ” — Sáàmù 130 : 5 - 7 .
Ki Isireli maa ba a niso ni diduro de Jehofa . " -- Saamu 130 : 5 - 7 .
Aṣọ ìkélé ti àgbàlá tí ó yí ibi mímọ́ ati pẹpẹ ká, aṣọ ìkélé fún ẹnu ọ̀nà àgbàlá, ati okùn wọn, ati gbogbo àwọn ohun tí wọn ń lò pẹlu wọn. Àwọn ni wọn óo máa ṣe oríṣìíríṣìí iṣẹ́ tí ó bá jẹ mọ́ àwọn nǹkan wọnyi.
Aso ikele ti agbala ti o yi ibi mimo ati pepe ka, aso ikele fun enu ona agbala, ati okun won, ati gbogbo awon ohun ti won n lo pelu won. Awon ni won oo maa se orisiirisii ise ti o ba je mo awon nnkan wonyi.
Wo àpilẹ̀kọ náà , “ Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .
Wo apileko naa , “ Awon Odo Beere Pe . . .
Lẹ́yìn wọn ni Benjamini àti Haṣubu tún èyí ti iwájú ilé wọn ṣe; lẹ́yìn wọn ni, Asariah ọmọ Maaseiah ọmọ Ananiah tún ti ẹ̀gbẹ́ ilé rẹ̀ ṣe.
Leyin won ni Benjamini ati Hasubu tun eyi ti iwaju ile won se; leyin won ni, Asariah omo Maaseiah omo Ananiah tun ti egbe ile re se.
Nítorí , bí ọ̀kan nínú wọn bá ṣubú , èkejì lè gbé alábàákẹ́gbẹ́ rẹ̀ dìde . ”
Nitori , bi okan ninu won ba subu , ekeji le gbe alabaakegbe re dide . "
Kì í ṣe ìwọ nìkan o .
Ki i se iwo nikan o .
Lẹ́yìn náà , ẹ̀mí mímọ́ kó ipa pàtàkì nínú yíyan Bánábà àti Sọ́ọ̀lù ( àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù ) fún iṣẹ́ míṣọ́nnárì , ó sì tún darí wọn láti mọ ibi tó yẹ kí wọ́n lọ àti ibi tí kò yẹ kí wọ́n lọ .
Leyin naa , emi mimo ko ipa pataki ninu yiyan Banaba ati Soolu ( apositeli Poolu ) fun ise misonnari , o si tun dari won lati mo ibi to ye ki won lo ati ibi ti ko ye ki won lo .
• Pípa ilẹ̀ ayé run
• Pipa ile aye run
Dídọ́gbẹ́ Síra Ẹni Lára
Didogbe Sira Eni Lara
Mikaiah sì dáhùn pé, “Mo rí gbogbo Israẹli túká kiri lórí àwọn òkè bí àgùntàn tí kò ní olùṣọ́, sì wí pé, ‘Àwọn wọ̀nyí kò ní olúwa. Jẹ́ kí olúkúlùkù padà sí ilé rẹ̀ ní àlàáfíà.’ ”
Mikaiah si dahun pe, “Mo ri gbogbo Israeli tuka kiri lori awon oke bi aguntan ti ko ni oluso, si wi pe, ‘Awon wonyi ko ni oluwa. Je ki olukuluku pada si ile re ni alaafia.’ ”
Nígbà náà ni Jésù ti Gálílì wá sí odò Jọ́dánì kí Jòhánù báà lè ṣe ìtẹ̀bọmi fún un
Nigba naa ni Jesu ti Galili wa si odo Jodani ki Johanu baa le se itebomi fun un
Bá aya arákùnrin ọkọ rẹ tí ó ti di opó padà . ”
Ba aya arakunrin oko re ti o ti di opo pada . "
Olùkọ́ àwọn adití kan sọ fún wa pé Kristi máa nílò àkànṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ .
Oluko awon aditi kan so fun wa pe Kristi maa nilo akanse idanilekoo .
Kí nìdí tí kò fi yẹ kó o bẹ̀rù tàbí fà sẹ́yìn láti ya ara rẹ sí mímọ́ ?
Ki nidi ti ko fi ye ko o beru tabi fa seyin lati ya ara re si mimo ?
Ìpọ́njú Bá Orílẹ̀ - Èdè Ísírẹ́lì
Iponju Ba Orile - Ede Isireli
Kí ni ìdájọ́ tí Ilé Ẹjọ́ ṣe yìí máa ṣe fún òmìnira ìsìn àwọn olùgbé Rọ́ṣíà ?
Ki ni idajo ti Ile Ejo se yii maa se fun ominira isin awon olugbe Rosia ?
Alóre sì kọ sí ẹni tí ń ṣọ́ bodè, ó sì wí pe, Wò ó, ọkùnrin kan ń sáré òun nìkan
Alore si ko si eni ti n so bode, o si wi pe, Wo o, okunrin kan n sare oun nikan
Àmọ́ ṣá o , ńṣe ni Gòláyátì fi ọwọ́ ara rẹ̀ ṣera ẹ̀ bó ṣe ń pẹ̀gàn ẹgbẹ́ ológun àwọn èèyàn Jèhófà .
Amo sa o , nse ni Golayati fi owo ara re sera e bo se n pegan egbe ologun awon eeyan Jehofa .
mẹta. Ìyẹn jẹ ìtanràn ìbúra yín
meta. Iyen je itanran ibura yin
Kí ni ìpíndọ́gba gígùn ẹ̀mí àwọn èèyàn , àwọn ọdún wa sì kún fún kí ni ?
Ki ni ipindogba gigun emi awon eeyan , awon odun wa si kun fun ki ni ?