diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
▪ Lára àwọn ọmọ ọdún méjìlá sí ọmọ ogún ọdún tí wọ́n ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì lórílẹ̀ - èdè Netherlands , tí wọ́n ṣèbẹ̀wò síbì kan tí wọ́n ti lè fi ẹ̀rọ tó ń ya fọ́tò polówó ara wọn lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì , “ nǹkan bí ìdajì ọmọkùnrin àti ìdajì ó lé díẹ̀ lára àwọn ọmọbìnrin tó wà lára wọn sọ pé wọ́n ní káwọn bọ́ra síhòòhò tàbí káwọn ṣe bí aṣẹ́wó lóríṣiríṣi ọ̀nà níwájú ẹ̀rọ tó ń ya fọ́tò náà . ” — RUTGERS NISSO GROEP , ORÍLẸ̀ - ÈDÈ NETHERLANDS .
▪ Lara awon omo odun mejila si omo ogun odun ti won n lo Intaneeti lorile - ede Netherlands , ti won sebewo sibi kan ti won ti le fi ero to n ya foto polowo ara won lori Intaneeti , “ nnkan bi idaji omokunrin ati idaji o le die lara awon omobinrin to wa lara won so pe won ni kawon bora sihooho tabi kawon se bi asewo lorisirisi ona niwaju ero to n ya foto naa . ” — RUTGERS NISSO GROEP , ORILE - EDE NETHERLANDS .
Àmọ́ , Jésù fi hàn wá pé àwa náà lè fọgbọ́n mọ àwọn ohun tẹ́nì kan nífẹ̀ẹ́ sí , àti ohun tó ń mú un ṣe àwọn ohun tó ń ṣe , títí kan àwọn ohun tó fi ṣáájú .
Amo , Jesu fi han wa pe awa naa le fogbon mo awon ohun teni kan nifee si , ati ohun to n mu un se awon ohun to n se , titi kan awon ohun to fi saaju .
òfò.
ofo.
Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ wọ́n sì ba Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ nínú jẹ́
Sibesibe won sote won si ba Emi Mimo re ninu je
Ojú ẹsẹ̀ yẹn ni ọ̀gá mi gbaṣẹ́ lọ́wọ́ mi .
Oju ese yen ni oga mi gbase lowo mi .
òun sì kẹ́gàn rẹ̀ ní ọkàn rẹ̀
oun si kegan re ni okan re
dìhámọ́ra
dihamora
Ara nǹkan tí wọ́n máa ń ṣe nínú ìjọsìn wọn ni fífi ìlẹ̀kẹ̀ gbàdúrà sí Màríà Wúńdíá .
Ara nnkan ti won maa n se ninu ijosin won ni fifi ileke gbadura si Maria Wundia .
Níwọ̀n bí àwọn èèyàn ti máa ń fi òkùnkùn bojú ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ ibi , òru lè jẹ́ àkókò ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ .
Niwon bi awon eeyan ti maa n fi okunkun boju se opo ise ibi , oru le je akoko erujeje .
Àwọn ìpolówó ọjà àtàwọn eré ìnàjú kan nínú ayé oníwà pálapàla yìí máa ń fi hàn pé àwọn ọmọdé lóye ìbálòpọ̀ dáadáa , pé kò sí ohun téèyàn lè fi bò fún wọn níbẹ̀ .
Awon ipolowo oja atawon ere inaju kan ninu aye oniwa palapala yii maa n fi han pe awon omode loye ibalopo daadaa , pe ko si ohun teeyan le fi bo fun won nibe .
Èyí ni majẹmu tí mo bá gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà láyé dá.”
Eyi ni majemu ti mo ba gbogbo eda alaaye ti o wa laye da."
méjéẹ̀jì ohun tí wọn fi n ṣe òòyà
mejeeji ohun ti won fi n se ooya
Ǹjẹ́ O Lè Ṣe Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira ?
Nje O Le Se Bii Ti Finihasi Bo O Ba Doju Ko Awon Ipo To Nira ?
Nítorí náà, mo sọ fun yín pé ẹ kò ní fojú kàn mí mọ́ títí di àkókò tí ẹ óo wí pé, ‘Olùbùkún ni ẹni tí ń bọ̀ wá ní orúkọ Oluwa!’ ”
Nitori naa, mo so fun yin pe e ko ni foju kan mi mo titi di akoko ti e oo wi pe, 'Olubukun ni eni ti n bo wa ni oruko Oluwa!' "
Lẹ́yìn náà , “ àwọn ènìyàn náà sì bẹ̀rẹ̀ sí bẹ̀rù Jèhófà , wọ́n sì ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà àti Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀ . ” — Ẹ́kís .
Leyin naa , “ awon eniyan naa si bere si beru Jehofa , won si ni igbagbo ninu Jehofa ati Mose iranse re . ” — Ekis .
Mo sì mọrírì ìtìlẹ́yìn ráńpẹ́ tí mo láǹfààní láti máa ṣe lọ́nà yìí fún ẹgbẹ́ ará tó wà kárí ayé .
Mo si moriri itileyin ranpe ti mo lanfaani lati maa se lona yii fun egbe ara to wa kari aye .
Ṣùgbọ́n báwo la ó ṣe tọ́ irú ẹni bẹ́ẹ̀ sọ́nà padà ?
Sugbon bawo la o se to iru eni bee sona pada ?
Bí ọkùnrin kan bá ń bọ́ ẹran ọ̀sìn rẹ̀ lórí pápá tàbí nínú ọgbà àjàrà, tí ó sì jẹ́ kí ó lọ jẹ nínú oko ẹlòmíràn, a ó mú kí ó san ohun ti ẹran rẹ̀ jẹ padà pẹ̀lú èyí tí ó dára jù nínú oko tàbí nínú ọgbà rẹ̀
Bi okunrin kan ba n bo eran osin re lori papa tabi ninu ogba ajara, ti o si je ki o lo je ninu oko elomiran, a o mu ki o san ohun ti eran re je pada pelu eyi ti o dara ju ninu oko tabi ninu ogba re
• Kí nìdí tí àdúrà àti ẹ̀mí mímọ́ fi ṣe pàtàkì nínú iṣẹ́ ìsìn wa sí Jèhófà ?
• Ki nidi ti adura ati emi mimo fi se pataki ninu ise isin wa si Jehofa ?
Ọlọ́run ìṣòtítọ́ , ẹni tí kò sí àìṣèdájọ́ òdodo lọ́dọ̀ rẹ̀ ; Olódodo àti adúróṣánṣán ni . ” ​ — Diu .
Olorun isotito , eni ti ko si aisedajo ododo lodo re ; Olododo ati adurosansan ni . " -- Diu .
Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó-lé-méjì (642)
Bani je ojilelegbeta o-le-meji (642)
Bí wọ́n sì ti ń sọ nǹkan wọ̀nyí Jesu tìkára rẹ̀ dúró láàrín wọn, ó sì wí fún wọn pé,
Bi won si ti n so nnkan wonyi Jesu tikara re duro laarin won, o si wi fun won pe,
Kí nìdí tó fi lè jẹ́ pé dídá tí Pétérù dá ara rẹ̀ lójú jù ló mú kó ṣe àṣìṣe yìí ?
Ki nidi to fi le je pe dida ti Peteru da ara re loju ju lo mu ko se asise yii ?
Ó lè jẹ́ pé o kàn fẹ́ “ sinmi díẹ̀ ” ni .
O le je pe o kan fe " sinmi die " ni .
Ká tó lè dáhùn ìbéèrè pàtàkì yẹn , ẹ jẹ́ ká ṣàyẹ̀wò àpèjúwe méjì tí Jésù sọ nípa ìdí tó fi yẹ ká máa “ so èso . ”
Ka to le dahun ibeere pataki yen , e je ka sayewo apejuwe meji ti Jesu so nipa idi to fi ye ka maa “ so eso . ”
Àmọ́ , kí ló máa jẹ́ kó dá wa lójú pé ọ̀rọ̀ inú ìwé Hágáì àti Sekaráyà kàn wá lóde òní ?
Amo , ki lo maa je ko da wa loju pe oro inu iwe Hagai ati Sekaraya kan wa lode oni ?
Òun àti Sámúẹ́lì lọ sí Náíótì láti dúró níbẹ̀
Oun ati Samueli lo si Naioti lati duro nibe
Àwọn Èèyàn Àlàáfíà Gbèjà Orúkọ Rere Wọn
Awon Eeyan Alaafia Gbeja Oruko Rere Won
A máa ń gbádùn ìkẹ́kọ̀ọ́ náà gan - an ni .
A maa n gbadun ikekoo naa gan - an ni .
• Àwọn wo ni “ àwọn ohun tí ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé , ” kí sì ni ìrètì àwọn wọ̀nyẹn ?
• Awon wo ni “ awon ohun ti n be lori ile aye , ” ki si ni ireti awon wonyen ?
ìbẹ̀rù kò má baà tẹ̀tẹ̀ tán nítorí pé
iberu ko ma baa tete tan nitori pe
  Olúwa sọ fún Mósè, Sọ fún Árónì, Mú ọ̀pá rẹ kí ó sì na ọwọ́ rẹ jáde lórí àwọn omi Éjíbítì
  Oluwa so fun Mose, So fun Aroni, Mu opa re ki o si na owo re jade lori awon omi Ejibiti
Kí n tó lọ sí Tẹsalóníkà , mo lọ sí ṣọ́ọ̀bù obìnrin kan tó ń ránṣọ ní Kọ́ríńtì , láti lọ rán ẹ̀wù àwọ̀lékè kan .
Ki n to lo si Tesalonika , mo lo si soobu obinrin kan to n ranso ni Korinti , lati lo ran ewu awoleke kan .
Ṣebí ọjọ́ díẹ̀ ni mo níláti lò láyé?Fi mí sílẹ̀ kí n lè ní ìtura díẹ̀,
Sebi ojo die ni mo nilati lo laye?Fi mi sile ki n le ni itura die,
Níbẹ̀ ni ẹ ó wa rántí ìwà àti gbogbo ìsesí yín, èyí tí ẹ̀yin fi sọ ara yín di aláìmọ́, ẹ̀yin yóò sì kóríra ara yín fún gbogbo ibi tí ẹ̀yin ti se
Nibe ni e o wa ranti iwa ati gbogbo isesi yin, eyi ti eyin fi so ara yin di alaimo, eyin yoo si korira ara yin fun gbogbo ibi ti eyin ti se
Wọ́n kọ ọ́ gàdàgbà sí ọ̀kan nínú àwọn ojú ìwé ìbẹ̀rẹ̀ Bíbélì náà pé Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run .
Won ko o gadagba si okan ninu awon oju iwe ibere Bibeli naa pe Jehofa ni oruko Olorun .
Lóòótọ́ , ìwé mímọ́ àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí kọ́ni pé Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà , ó sì sọ pé ó mọ ohun gbogbo àti pé ó máa ń mọ ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀ , àmọ́ kò sí ibì kankan tó ti sọ pé Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run , èyí tó fara hàn ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún ìgbà nínú Bíbélì .
Loooto , iwe mimo awon elesin Musulumi koni pe Olorun kan soso lo wa , o si so pe o mo ohun gbogbo ati pe o maa n mo ohun ti ko tii sele , amo ko si ibi kankan to ti so pe Jehofa ni oruko Olorun , eyi to fara han ni egbeegberun igba ninu Bibeli .
Ṣùgbọ́n , àwọn ìwà kan ò rọrùn fún mi rárá láti yí pa dà .
Sugbon , awon iwa kan o rorun fun mi rara lati yi pa da .
Irú àwọn ìròyìn kòbákùngbé bí ìwọ̀nyí tí mú káwọn tó ń ṣètọrẹ àánú túbọ̀ wà lójúfò nípa iye tí wọ́n fi ń tọrẹ àti ẹni tí wọ́n ń kó ọrẹ náà fún .
Iru awon iroyin kobakungbe bi iwonyi ti mu kawon to n setore aanu tubo wa lojufo nipa iye ti won fi n tore ati eni ti won n ko ore naa fun .
12 , 13 .
12 , 13 .
50 : 15 - 21 .
50 : 15 - 21 .
Níwọ̀n bí ẹ̀sùn tí Èṣù fi kan Jóòbù yìí ti mú kí ọ̀ràn tó ń fa wàhálà lé lórí gan - an túbọ̀ ṣe kedere , ẹ jẹ́ ká fara balẹ̀ gbé ọ̀ràn náà yẹ̀ wò .
Niwon bi esun ti Esu fi kan Joobu yii ti mu ki oran to n fa wahala le lori gan - an tubo se kedere , e je ka fara bale gbe oran naa ye wo .
Ní ọjọ́ keji, Paulu mú àwọn ọkunrin náà, ó ṣe ètò láti wẹ ẹ̀jẹ́ wọn kúrò, ati tirẹ̀ pẹlu. Ó wọ Tẹmpili lọ láti lọ ṣe ìfilọ̀ ọjọ́ tí àkókò ìwẹ̀nùmọ́ wọn yóo parí, tí òun yóo mú ọrẹ ti ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn wá.
Ni ojo keji, Paulu mu awon okunrin naa, o se eto lati we eje won kuro, ati tire pelu. O wo Tempili lo lati lo se ifilo ojo ti akoko iwenumo won yoo pari, ti oun yoo mu ore ti enikookan won wa.
Lẹ́yìn tó ka Fílípì 4 : 6 , 7 ní àkàtúnkà , ó sa gbogbo ipá rẹ̀ láti fi ìmọ̀ràn tó wà níbẹ̀ sílò .
Leyin to ka Filipi 4 : 6 , 7 ni akatunka , o sa gbogbo ipa re lati fi imoran to wa nibe silo .
nítorí tí Abrahamu gba ohùn mi gbọ́, ó sì pa gbogbo ìkìlọ̀, àṣẹ, ìlànà àti òfin mi mọ́.”
nitori ti Abrahamu gba ohun mi gbo, o si pa gbogbo ikilo, ase, ilana ati ofin mi mo.”
Egbe agbaboolu African Continental Bank tabi nìkan ACB FC jẹ ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria ti o wa ni Lagos .
Egbe agbaboolu African Continental Bank tabi nikan ACB FC je egbe agbaboolu Naijiria ti o wa ni Lagos .
Àwọn Kristẹni tòótọ́ ní láti “ dúró , àní ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́ , de ìgbàlà Jèhófà . ”
Awon Kristeni tooto ni lati “ duro , ani ni idakejee , de igbala Jehofa . ”
Lẹ́yìn ìyẹn , Jèhófà máa fi àánú hàn sí wa torí pé ó máa ń dárí jini lọ́pọ̀lọpọ̀ . — Aísá .
Leyin iyen , Jehofa maa fi aanu han si wa tori pe o maa n dari jini lopolopo . -- Aisa .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò dùn mọ́ wọn nínú pé wọn kò bímọ , wọ́n jùmọ̀ ń bá a nìṣó láti máa fi òótọ́ sin Jèhófà .
Bo tile je pe ko dun mo won ninu pe won ko bimo , won jumo n ba a niso lati maa fi ooto sin Jehofa .
Àmọ́ , ó bani nínú jẹ́ pé ó ṣòro fáwọn kan láti fi ìgbésí ayé tó ti mọ́ wọn lára sílẹ̀ .
Amo , o bani ninu je pe o soro fawon kan lati fi igbesi aye to ti mo won lara sile .
[ Àpótí tó wà ní ojú ìwé 19 ]
[ Apoti to wa ni oju iwe 19 ]
pìwàdà, nígbà náà tiyín ni ojú-
piwada, nigba naa tiyin ni oju-
[ Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 21 ]
[ Aworan Credit Line to wa ni oju iwe 21 ]
fara-ìjà
fara-ija
Jèhófà ni “ Olùgbọ́ àdúrà . ”
Jehofa ni " Olugbo adura . "
Ó ṣeé ṣe kóo fẹ́ wádìí kínníkínní nípa bó ṣe rí àti ọgbọ́n tó ń lò .
O see se koo fe wadii kinnikinni nipa bo se ri ati ogbon to n lo .
nípa ìjọsìn yín.
nipa ijosin yin.
Tá a bá ń fọkàn yàwòrán ohun tí Ọlọ́run ti ṣèlérí pé òun máa ṣe , ohun tó dájú pé ó máa ṣẹlẹ̀ là ń fọkàn rò yẹn . — 2 Pét .
Ta a ba n fokan yaworan ohun ti Olorun ti seleri pe oun maa se , ohun to daju pe o maa sele la n fokan ro yen . — 2 Pet .
Nítorí ìdí èyí, Jakọbu di ọlọ́rọ̀ gidigidi, agbo ẹran rẹ̀ pọ̀ àti àwọn ìránṣẹ́kùnrin, ìránṣẹ́bìnrin pẹ̀lú ìbákasẹ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.
Nitori idi eyi, Jakobu di oloro gidigidi, agbo eran re po ati awon iransekunrin, iransebinrin pelu ibakase ati ketekete.
Marie gbà gbọ́ pé “ àwọn ẹni mímọ́ ” lè ran òun lọ́wọ́ bí òun bá gbàdúrà sí wọn .
Marie gba gbo pe " awon eni mimo " le ran oun lowo bi oun ba gbadura si won .
Ó túbọ̀ ń ṣòro fáwọn òbí níbi gbogbo láti tọ́ àwọn ọmọ wọn .
O tubo n soro fawon obi nibi gbogbo lati to awon omo won .
Faloye gba àmì-ẹ̀yẹ ti NAACP Image Award for Outstanding Supporting Actress in a Drama Series ní ọdún 1996 fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Chantel Tierney nínu eré New York Undercover.[1] Faloye tún ti ní àwọn ipa nínu eré tẹlifíṣọ̀nù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Law & Order.
Faloye gba ami-eye ti NAACP Image Award for Outstanding Supporting Actress in a Drama Series ni odun 1996 fun ipa re gege bi Chantel Tierney ninu ere New York Undercover.[1] Faloye tun ti ni awon ipa ninu ere telifisonu ti akole re je Law & Order.
tí ẹ̀yin ó bá sì ṣe ẹbọ iná sí ẹbọ sísun, tàbí ẹbọ, láti san ẹ̀jẹ́ pàtàkì tàbí ọrẹ àtinúwá, tàbí nínú àjọ yín, láti ṣe òórùn dídùn sí nínú agbo ẹran tàbí ọ̀wọ́ ẹran,
ti eyin o ba si se ebo ina si ebo sisun, tabi ebo, lati san eje pataki tabi ore atinuwa, tabi ninu ajo yin, lati se oorun didun si ninu agbo eran tabi owo eran,
Ẹ wá àwọn nǹkan tuntun tẹ́ ẹ lè jọ máa ṣe .
E wa awon nnkan tuntun te e le jo maa se .
Bàbá mi ṣe jangirọ́fà kan fún mi , mo sì fẹ́ràn láti máa sáré kiri inú ọgbà .
Baba mi se jangirofa kan fun mi , mo si feran lati maa sare kiri inu ogba .
Ìgbà wo lo kọ́kọ́ mọ̀ nípa ìfẹ́ Jèhófà ?
Igba wo lo koko mo nipa ife Jehofa ?
Àwọn ayékòótọ́ tó bá ń gbé inú igbó lè lò tó ọgbọ̀n [ 30 ] ọdún sí ogójì [ 40 ] ọdún láyé .
Awon ayekooto to ba n gbe inu igbo le lo to ogbon [ 30 ] odun si ogoji [ 40 ] odun laye .
Tó bá rí ohun gidi gbé ṣe , ọjọ́ ikú rẹ̀ sàn ju ọjọ́ tí wọ́n bí i lọ fíìfíì nìyẹn , nítorí pé lọ́jọ́ tí wọ́n bí i , ẹnì kankan ò tíì mọ ohun tó máa gbélé ayé ṣe .
To ba ri ohun gidi gbe se , ojo iku re san ju ojo ti won bi i lo fiifii niyen , nitori pe lojo ti won bi i , eni kankan o tii mo ohun to maa gbele aye se .
Ṣùgbọ́n ojú Pétérù àti ti àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ wúwo fún oorun
Sugbon oju Peteru ati ti awon ti n be lodo re wuwo fun oorun
Rèbékà ní kí Élíésérì àtàwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ wá sílé àwọn kí wọ́n lè “ sùn mọ́jú . ”
Rebeka ni ki Elieseri atawon to wa pelu re wa sile awon ki won le “ sun moju . ”
Ọkùnrin tó fún irúgbìn nínú àpèjúwe yìí ṣàpẹẹrẹ akéde Ìjọba Ọlọ́run kọ̀ọ̀kan .
Okunrin to fun irugbin ninu apejuwe yii sapeere akede Ijoba Olorun kookan .
Jésù Kristi jẹ́ àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù , òun sì ni ẹni tí a ó tipasẹ̀ rẹ̀ bù kún aráyé onígbọràn .
Jesu Kristi je atomodomo Aburahamu , oun si ni eni ti a o tipase re bu kun araye onigboran .
Dáníẹ́lì àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ olùbẹ̀rù Ọlọ́run ti pinnu láti rọ̀ mọ́ òfin Jèhófà kó tó di pé wọ́n fẹ́ fagbára mú wọn jẹ àwọn oúnjẹ adùnyùngbà ọba .
Danieli atawon ore re oluberu Olorun ti pinnu lati ro mo ofin Jehofa ko to di pe won fe fagbara mu won je awon ounje adunyungba oba .
6. Njẹ ẹ̀rí tò dájú kò ha fi bẹ nínú
6. Nje eri to daju ko ha fi be ninu
30. Ki àwọn ẹ̀nìyàn oní ìwé baà
30. Ki awon eniyan oni iwe baa
Ṣugbọn Ọlọrun ti yan àwọn nǹkan tí ayé kà sí agọ̀ láti fi dójú ti àwọn ọlọ́gbọ́n, ó yan àwọn nǹkan tí kò lágbára ti ayé, láti fi dójú ti àwọn alágbára;
Sugbon Olorun ti yan awon nnkan ti aye ka si ago lati fi doju ti awon ologbon, o yan awon nnkan ti ko lagbara ti aye, lati fi doju ti awon alagbara;
Ó sọ pé : “ Mi ò lè dá iṣẹ́ tí mò ń ṣe dúró o , àmọ́ jọ̀ọ́ wábi fìdí lé kó o máa sọ̀rọ̀ rẹ ǹṣó . ”
O so pe : " Mi o le da ise ti mo n se duro o , amo joo wabi fidi le ko o maa soro re nso . "
Báwọn ọmọ yín bá ń lo tẹlifóònù alágbèéká , àwọn ọ̀nà wo lẹ lè gbà kọ́ wọn láti máa ṣọ́ra ṣe ?
Bawon omo yin ba n lo telifoonu alagbeeka , awon ona wo le le gba ko won lati maa sora se ?
Bi ó bá jẹ́ ijà nítorí ilẹ̀ oko
Bi o ba je ija nitori ile oko
O lè bá ẹni náà jíròrò díẹ̀ lára ohun tí ìṣẹ̀dá jẹ́ ká mọ̀ nípa agbára àti ọgbọ́n Ẹlẹ́dàá bá a ṣe ṣàlàyé rẹ̀ lábẹ́ ìsọ̀rí méjì tó kàn .
O le ba eni naa jiroro die lara ohun ti iseda je ka mo nipa agbara ati ogbon Eledaa ba a se salaye re labe isori meji to kan .
Solomoni ọba ati gbogbo àwọn ọmọ Israẹli péjọ níwájú Àpótí Ẹ̀rí OLUWA, wọ́n sì fi ọpọlọpọ aguntan ati mààlúù tí ẹnikẹ́ni kò lè kà rúbọ.
Solomoni oba ati gbogbo awon omo Israeli pejo niwaju Apoti Eri OLUWA, won si fi opolopo aguntan ati maaluu ti enikeni ko le ka rubo.
Gbogbo wa pátá ni Mọ́mì sọ nípa ohun tó ń kọ́ látinú Bíbélì fún .
Gbogbo wa pata ni Momi so nipa ohun to n ko latinu Bibeli fun .
Ṣé àkókò kúkúrú kan là óò fi wà láàyè ni ?
Se akoko kukuru kan la oo fi wa laaye ni ?
“Mo ti fi orúkọ rẹ han àwọn eniyan tí o fún mi ninu ayé. Tìrẹ ni wọ́n, ìwọ ni o wá fi wọ́n fún mi. Wọ́n sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.
“Mo ti fi oruko re han awon eniyan ti o fun mi ninu aye. Tire ni won, iwo ni o wa fi won fun mi. Won si ti pa oro re mo.
Ìwé ìròyìn The Star ti ìlú Johannesburg kìlọ̀ pé : “ Gúúsù Áfíríkà lè di orílẹ̀ - èdè àwọn ọ̀mùtí paraku , nítorí bí àwọn ọmọdé ṣe ń dẹni tó ń mu ọtí ìmukúmu nígbà tọ́jọ́ orí wọn ṣì kéré gan - an . ”
Iwe iroyin The Star ti ilu Johannesburg kilo pe : " Guusu Afirika le di orile - ede awon omuti paraku , nitori bi awon omode se n deni to n mu oti imukumu nigba tojo ori won si kere gan - an . "
Ṣùgbọ́n ìyẹn kò ní kó o wá máa bẹ̀rù Èṣù o .
Sugbon iyen ko ni ko o wa maa beru Esu o .
Nígbà tó ṣì jẹ́ ọ̀dọ́ , wọ́n kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́ “ nínú gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Íjíbítì . ”
Nigba to si je odo , won ko o lekoo “ ninu gbogbo ogbon awon ara Ijibiti . ”
( Láti rí bá a ṣe to ọ̀rọ̀ sójú ìwé , wo ìtẹ̀jáde náà gan - an )
( Lati ri ba a se to oro soju iwe , wo itejade naa gan - an )
Apá ti ilẹ̀ ayé lára ètò Jèhófà Ọlọ́run yìí náà ń yára sáré .
Apa ti ile aye lara eto Jehofa Olorun yii naa n yara sare .
wỌn kí wọn lẹ̀ rẹ̀ ara wọn síjlẹ̀.
wOn ki won le re ara won sijle.
Àwọn wo ni Jèhófà kó jọ tó wá fi rọ́pò orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì apẹ̀yìndà , kí wọ́n lè máa gbé orúkọ rẹ̀ ga ?
Awon wo ni Jehofa ko jo to wa fi ropo orile - ede Isireli apeyinda , ki won le maa gbe oruko re ga ?
Látijọ́ , ara àpáàdì yìí làwọn èèyàn máa ń kọ̀wé sí lọ́pọ̀ ibi ní Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn , títí kan ilẹ̀ Íjíbítì àti Mesopotámíà , torí pé ó rọrùn láti rí .
Latijo , ara apaadi yii lawon eeyan maa n kowe si lopo ibi ni Aarin Gbungbun Ila Oorun , titi kan ile Ijibiti ati Mesopotamia , tori pe o rorun lati ri .
Nígbà kan tí wọ́n bi wọ́n pé kí ló mú kí wọ́n di aṣáájú ọ̀nà , ìyẹn àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó máa ń fi ọ̀pọ̀ àkókò wàásù , wọ́n dáhùn pé : “ A rí i pé iṣẹ́ aṣáájú ọ̀nà tí màmá wa ń ṣe ń fún un láyọ̀ gan - an , àwa náà sì fẹ́ láyọ̀ bíi tirẹ̀ . ”
Nigba kan ti won bi won pe ki lo mu ki won di asaaju ona , iyen awon Elerii Jehofa to maa n fi opo akoko waasu , won dahun pe : " A ri i pe ise asaaju ona ti mama wa n se n fun un layo gan - an , awa naa si fe layo bii tire . "
Ṣùgbọ́n ohun tí Olúwa wí níyìí
Sugbon ohun ti Oluwa wi niyii
Ọdọmọkunrin kan tí ó ń jẹ́ Yutiku jókòó lórí fèrèsé. Ó ti sùn lọ níbi tí Paulu gbé ń sọ̀rọ̀ lọ títí. Nígbà tí oorun wọ̀ ọ́ lára, ó ré bọ́ sílẹ̀ láti orí pẹ̀tẹ́ẹ̀sì kẹta. Nígbà tí wọn óo gbé e, ó ti kú.
Odomokunrin kan ti o n je Yutiku jokoo lori ferese. O ti sun lo nibi ti Paulu gbe n soro lo titi. Nigba ti oorun wo o lara, o re bo sile lati ori peteesi keta. Nigba ti won oo gbe e, o ti ku.
Ó wá dà bíi pé wọ́n ti sọ àdúrà di “ oògùn amáratuni . ”
O wa da bii pe won ti so adura di " oogun amaratuni . "
Ẹ ranti ohun tí ó ṣe sí àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Ijipti ati sí àwọn ẹṣin wọn ati kẹ̀kẹ́ ogun wọn; bí ó ti jẹ́ kí omi Òkun Pupa bò wọ́n mọ́lẹ̀ nígbà tí wọ́n ń le yín bọ̀, ati bí OLUWA ti pa wọ́n run títí di òní olónìí.
E ranti ohun ti o se si awon omo ogun ile Ijipti ati si awon esin won ati keke ogun won; bi o ti je ki omi Okun Pupa bo won mole nigba ti won n le yin bo, ati bi OLUWA ti pa won run titi di oni olonii.
Kódà , ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ kan tó ya àwọn tó ń bá sọ̀rọ̀ lẹ́nu , ó ní Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì tó wà níbẹ̀ máa pa run .
Koda , o so asotele kan to ya awon to n ba soro lenu , o ni Jerusalemu ati tenpili to wa nibe maa pa run .
Téèyàn bá gba ilẹ̀ tó ń yọ̀ kọjá , á fẹ́ di nǹkan mú kó má báa yọ̀ ṣubú .
Teeyan ba gba ile to n yo koja , a fe di nnkan mu ko ma baa yo subu .
Lọ́pọ̀ ibi , àwọn ìdílé kò rí àlékún kankan nínú iye tó ń wọlé fún wọn láti àádọ́ta ọdún sẹ́yìn , nígbà tó sì jẹ́ pé ìlọ́po ìlọ́po ni iye owó tó ń wọlé fún àwọn mìíràn .
Lopo ibi , awon idile ko ri alekun kankan ninu iye to n wole fun won lati aadota odun seyin , nigba to si je pe ilopo ilopo ni iye owo to n wole fun awon miiran .