diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Rẹ̀ àti àwọn onígbàgbọ òdodo, O
Re ati awon onigbagbo ododo, O
sì mú ẹṣẹ̀ wọn dìrò mọ ẹrọ ìpayà
si mu ese won diro mo ero ipaya
(Allah), òyí tô JẸ àwọn ni wọn
(Allah), oyi to JE awon ni won
lẹtọ sí i jùlọ, tí 0 sì yẹ fún wọn.
leto si i julo, ti 0 si ye fun won.
Allah sì ni Olùmọò ohun gbogbo
Allah si ni Olumoo ohun gbogbo
pátápátá.
patapata.
28. Dájúdájú, Allah ti sọ ìran náà
28. Dajudaju, Allah ti so iran naa
di òdodo fún Òjíṣẹ Rẹ̀. Dájúdájú
di ododo fun Ojise Re. Dajudaju
ẹ̀yin yòò wọ Mọṣalaáṣí Mímọ náà,
eyin yoo wo Mosalaasi Mimo naa,
bí Allah bá fẹ, pẹ̀lú ìfàyàbalẹ̀.
bi Allah ba fe, pelu ifayabale.
(àwọn kan) yòò fá ìrun orí (wọn).
(awon kan) yoo fa irun ori (won).
bẹ̀ẹ̀ ni (àwọn kan) yòò gé e mọlẹ̀;
bee ni (awon kan) yoo ge e mole;
ẹ kò sì ní bẹ̀rù. Ṣùgbôn Òun mọ
e ko si ni beru. Sugbon Oun mo
ohun tí ẹ̀yin kò mọ. Yàt(ọ sí ẹ̀yi.
ohun ti eyin ko mo. Yat(o si eyi.
Ò tún ti kọ ìṣẹgun kan tí 0 súnmọ
O tun ti ko isegun kan ti 0 sunmo
pẹkípẹkí mọ yín.
pekipeki mo yin.
29. Òun ni Ẹni tí Ò rán Òjíṣẹ Rẹ̀
29. Oun ni Eni ti O ran Ojise Re
pẹ̀lú ìtọsọnà àti Ẹsìn òdodo, kí Ô
pelu itosona ati Esin ododo, ki O
lò fi borí gbogbo ẹ̀sìn yòôkù.
lo fi bori gbogbo esin yooku.
Allah sì tô ní Ẹlẹrìí.
Allah si to ni Elerii.
30. Muhammad ni Òjíṣẹ: Allah
30. Muhammad ni Ojise: Allah
náà, àwọn tí 0 sì wà pẹ̀lú rẹ̀ fi ẹsẹ̀
naa, awon ti 0 si wa pelu re fi ese
wọn. tilẹ̀ ní àtakò sí àwọn
won. tile ni atako si awon
aláìgbàgbọ; wọn sì jẹ̀ ẹlẹ̀yinjú
alaigbagbo; won si je eleyinju
àánú sí ara wọn. Ìwọ máà nì rí
aanu si ara won. Iwo maa ni ri
wọn ní ìtẹríba àti ìforíbalẹ̀ (nínú
won ni iteriba ati iforibale (ninu
ìjọsìn). fún wíwá ojúure. àti
ijosin). fun wiwa ojuure. ati
ìdùnnú Allah. Àmì wọn tí í ṣe ipa
idunnu Allah. Ami won ti i se ipa
ìforíkanlẹ̀ f bẹ níwájú wọn. Éyí
iforikanle f be niwaju won. Eyi
Ninu ẹ̀yà Gadi, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé Ẹ̀yin ará mi, ṣé igi ọ̀pọ̀tọ́ lè so èso olifi, tabi kí àjàrà kó so ọ̀pọ̀tọ́? Ìsun omi kíkorò kò lè mú omi dídùn jáde.Kò ní náání oriṣa tí àwọn baba rẹ̀ ń sìn, kò sì ní bìkítà fún èyí tí àwọn obinrin fẹ́ràn; kò ní bìkítà fún oriṣa kankan, nítorí pé yóo gbé ara rẹ̀ ga ju gbogbo wọn lọ. Òtítọ́ ni mò ń sọ, n kò purọ́, pé ohun tí a yàn mí láti jẹ́ akéde ati aposteli sí ni pé kí n jẹ́ olùkọ́ni fún àwọn tí kì í ṣe Juu nípa nǹkan tí ó jẹ mọ́ igbagbọ ati òtítọ́ Ọlọrun. Just one utterance by the masquerader Agán is sufficient to effect a great deal of wonders.
Ninu eya Gadi, awon ti won to eni ogun odun, ti won to lo soju ogun, gege bi akosile won ni idile-idile Eyin ara mi, se igi opoto le so eso olifi, tabi ki ajara ko so opoto? Isun omi kikoro ko le mu omi didun jade.Ko ni naani orisa ti awon baba re n sin, ko si ni bikita fun eyi ti awon obinrin feran; ko ni bikita fun orisa kankan, nitori pe yoo gbe ara re ga ju gbogbo won lo. Otito ni mo n so, n ko puro, pe ohun ti a yan mi lati je akede ati aposteli si ni pe ki n je olukoni fun awon ti ki i se Juu nipa nnkan ti o je mo igbagbo ati otito Olorun. Just one utterance by the masquerader Agan is sufficient to effect a great deal of wonders.
The truly competent person need not strain overmuch to accomplish much. Agán is one of the more formidable Yoruba masqueraders; he was traditionally employed to execute witches.
The truly competent person need not strain overmuch to accomplish much. Agan is one of the more formidable Yoruba masqueraders; he was traditionally employed to execute witches.
Iná ń ṣàn jáde bí odò níwájú rẹ̀.Ẹgbẹẹgbẹrun ọ̀nà ẹgbẹẹgbẹrun ni àwọn tí ń ṣe iranṣẹ fún un,ọ̀kẹ́ àìmọye sì ni àwọn tí wọ́n dúró níwájú rẹ̀.Ìdájọ́ bẹ̀rẹ̀, a sì ṣí àwọn ìwé sílẹ̀. Ìwọ ni mo fi pa olùṣọ́-aguntan ati agbo ẹran rẹ̀ rẹ́,ìwọ ni mo fi run àgbẹ̀ ati àwọn alágbàro rẹ̀,ìwọ ni mo fi ṣẹ́ apá àwọn gomina ati ti àwọn olórí ogun.”Ẹkẹwaa mú Ṣimei, òun ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin, ati àwọn arakunrin rẹ̀ jẹ́ mejila. Ẹni tí í bá máa ń sọ̀rọ̀ jàbùjàbù láìronú,ọ̀rọ̀ rẹ̀ dàbí kí á fi idà gún eniyan,ṣugbọn ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dàbí ẹni wo ọgbẹ́ sàn.Ó ní, “Bí àwọn eniyan wọnyi bá ń lọ rúbọ ní ilé OLUWA ní Jerusalẹmu, ọkàn gbogbo wọ́n lè tipa bẹ́ẹ̀ pada sẹ́yìn Rehoboamu, oluwa wọn; wọn óo sì pa mí, wọn óo sì pada tọ Rehoboamu, ọba Juda, lọ.”Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí àwọn abúlé tí ó wà lẹ́bàá ìlú Kesaria ti Filipi. Bí wọ́n ti ń lọ ní ọ̀nà, ó bi wọ́n pé, “Ta ni àwọn eniyan ń pè mí?”o óo sì lọ gbé e fún baba yín, kí ó jẹ ẹ́, kí ó baà lè súre fún ọ, kí ó tó kú.”OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, A sì ti fi àáké lé gbòǹgbò igi báyìí, nítorí náà, igikígi tí kò bá so èso rere ni a óo gé lulẹ̀, tí a óo fi dáná. OLUWA, má jẹ́ kí ọwọ́ àwọn eniyan burúkú tẹ ohun tí wọn ń wá;má jẹ́ kí èrò ọkàn wọn ṣẹ.As far as the broom is concerned it is taboo: one does not make kindling of broomsticks.
Ina n san jade bi odo niwaju re.Egbeegberun ona egbeegberun ni awon ti n se iranse fun un,oke aimoye si ni awon ti won duro niwaju re.Idajo bere, a si si awon iwe sile. Iwo ni mo fi pa oluso-aguntan ati agbo eran re re,iwo ni mo fi run agbe ati awon alagbaro re,iwo ni mo fi se apa awon gomina ati ti awon olori ogun.”Ekewaa mu Simei, oun ati awon omo re okunrin, ati awon arakunrin re je mejila. Eni ti i ba maa n soro jabujabu laironu,oro re dabi ki a fi ida gun eniyan,sugbon oro ologbon dabi eni wo ogbe san.O ni, “Bi awon eniyan wonyi ba n lo rubo ni ile OLUWA ni Jerusalemu, okan gbogbo won le tipa bee pada seyin Rehoboamu, oluwa won; won oo si pa mi, won oo si pada to Rehoboamu, oba Juda, lo.”Jesu ati awon omo-eyin re jade lo si awon abule ti o wa lebaa ilu Kesaria ti Filipi. Bi won ti n lo ni ona, o bi won pe, “Ta ni awon eniyan n pe mi?”o oo si lo gbe e fun baba yin, ki o je e, ki o baa le sure fun o, ki o to ku.”OLUWA tun ba mi soro, o ni, A si ti fi aake le gbongbo igi bayii, nitori naa, igikigi ti ko ba so eso rere ni a oo ge lule, ti a oo fi dana. OLUWA, ma je ki owo awon eniyan buruku te ohun ti won n wa;ma je ki ero okan won se.As far as the broom is concerned it is taboo: one does not make kindling of broomsticks.
Ọmọ rẹ̀ yìí ni Ọlọrun fi agbára Ẹ̀mí Mímọ́ yàn nígbà tí ó jí i dìde kúrò ninu òkú. Òun náà ni Jesu Kristi Oluwa wa, Nígbà tí Pilatu gbọ́ èyí, ó bèèrè bí ará Galili bá ni Jesu. Lẹ́yìn náà Labani sọ fún un pé, “O wá gbọdọ̀ máa sìn mí lásán nítorí pé o jẹ́ ìbátan mi? Sọ fún mi, èló ni o fẹ́ máa gbà?” Ọmọ Hẹrọdiasi obinrin bá wọlé, ó bọ́ sí agbo, ó bẹ̀rẹ̀ sí jó, inú Hẹrọdu ati ti àwọn tí ó wà níbi àsè náà dùn. Ọba sọ fún ọmọbinrin náà pé, “Bèèrè ohun tí o bá fẹ́, n óo fi í fún ọ.” Ọjọ́ ayé mi ń lọ bí òjìji àṣáálẹ́,mo sì ń rọ bíi koríko.kí á máa já ẹ̀tọ́ olódodo gbà lọ́wọ́ rẹ̀ níwájú Ọ̀gá Ògo,Àwọn ọmọ Lefi ni: Jeṣua, Binui ati Kadimieli; Ṣerebaya, Juda, ati Matanaya, tí òun pẹlu àwọn arakunrin rẹ̀ wà nídìí ètò àwọn orin ọpẹ́.Ṣugbọn n kò fẹ́ dá nǹkankan ṣe láìjẹ́ pé o lọ́wọ́ sí i, n kò fẹ́ kí ó jẹ́ pé túlààsì ni oore tí mo fẹ́ kí o ṣe. Inú rẹ ni mo fẹ́ kí ó ti wá.OLUWA Ọlọrun yín yóo máa tì wọ́n sẹ́yìn fun yín, yóo máa lé wọn kúrò níwájú yín, ẹ óo sì gba ilẹ̀ wọn bí OLUWA Ọlọrun yín ti ṣèlérí fun yín. Gùdùgudu-ú kan légbò kán-ín-kán-ín.
Omo re yii ni Olorun fi agbara Emi Mimo yan nigba ti o ji i dide kuro ninu oku. Oun naa ni Jesu Kristi Oluwa wa, Nigba ti Pilatu gbo eyi, o beere bi ara Galili ba ni Jesu. Leyin naa Labani so fun un pe, “O wa gbodo maa sin mi lasan nitori pe o je ibatan mi? So fun mi, elo ni o fe maa gba?” Omo Herodiasi obinrin ba wole, o bo si agbo, o bere si jo, inu Herodu ati ti awon ti o wa nibi ase naa dun. Oba so fun omobinrin naa pe, “Beere ohun ti o ba fe, n oo fi i fun o.” Ojo aye mi n lo bi ojiji asaale,mo si n ro bii koriko.ki a maa ja eto olododo gba lowo re niwaju Oga Ogo,Awon omo Lefi ni: Jesua, Binui ati Kadimieli; Serebaya, Juda, ati Matanaya, ti oun pelu awon arakunrin re wa nidii eto awon orin ope.Sugbon n ko fe da nnkankan se laije pe o lowo si i, n ko fe ki o je pe tulaasi ni oore ti mo fe ki o se. Inu re ni mo fe ki o ti wa.OLUWA Olorun yin yoo maa ti won seyin fun yin, yoo maa le won kuro niwaju yin, e oo si gba ile won bi OLUWA Olorun yin ti seleri fun yin. Gudugudu-u kan legbo kan-in-kan-in.
Ó wù mí bíi pé kí n wà lọ́dọ̀ yín nisinsinyii, kí n yí ohùn mi pada, nítorí ọ̀rọ̀ yín rú mi lójú.Nítorí pé ó ṣíwọ́ sókè sí Ọlọrun,o sì ṣe oríkunkun sí Olodumare,Lóòótọ́, “Ohun tí a bá fẹ́ ni a lè ṣe,” bí àwọn kan ti ń wí. Ṣugbọn kì í ṣe gbogbo nǹkan ni ó ń ṣe eniyan ní anfaani. “Ohun tí a bá fẹ́ ni a lè ṣe.” Ṣugbọn kì í ṣe gbogbo nǹkan tí a lè ṣe ni ó ń mú ìdàgbà wá. Esau bẹ̀rẹ̀ sí bẹ baba rẹ̀ pé, “Ṣé ìre kan ṣoṣo ni o ní lẹ́nu ni, baba mi? Áà! Súre fún èmi náà, baba mi.” Esau bá bẹ̀rẹ̀ sí sọkún. “Nisinsinyii, OLUWA Ọlọrun wa, ìwọ tí o kó àwọn eniyan rẹ jáde ní ilẹ̀ Ijipti pẹlu agbára ńlá, nítorí orúkọ rẹ tí à ń ranti títí di òní, a ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe nǹkan burúkú. OLUWA yóo máa ṣọ́ ọ, yóo sì dá a sí.Yóo ní ayọ̀ ní ilẹ̀ náà;OLUWA kò ní fi í lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ lọ́wọ́.Ẹ̀rù ba Dafidi nítorí pé Saulu ń wá ọ̀nà láti pa á.Dafidi ń gbé aṣálẹ̀ Sifi ni Horeṣi. Ọ̀nà àtigun òkè Heresi ni Gideoni gbà nígbà tí ó ń ti ojú ogun pada bọ̀. Ìmẹ́lẹ́ máa ń fa òṣì,ṣugbọn ẹni tí ó bá tẹpá mọ́ṣẹ́ yóo di ọlọ́rọ̀.Ọ̀rọ̀ tó dojú rú di ti ọlọ́rọ̀, ayé á dẹ̀hìn.
O wu mi bii pe ki n wa lodo yin nisinsinyii, ki n yi ohun mi pada, nitori oro yin ru mi loju.Nitori pe o siwo soke si Olorun,o si se orikunkun si Olodumare,Loooto, “Ohun ti a ba fe ni a le se,” bi awon kan ti n wi. Sugbon ki i se gbogbo nnkan ni o n se eniyan ni anfaani. “Ohun ti a ba fe ni a le se.” Sugbon ki i se gbogbo nnkan ti a le se ni o n mu idagba wa. Esau bere si be baba re pe, “Se ire kan soso ni o ni lenu ni, baba mi? Aa! Sure fun emi naa, baba mi.” Esau ba bere si sokun. “Nisinsinyii, OLUWA Olorun wa, iwo ti o ko awon eniyan re jade ni ile Ijipti pelu agbara nla, nitori oruko re ti a n ranti titi di oni, a ti se, a si ti se nnkan buruku. OLUWA yoo maa so o, yoo si da a si.Yoo ni ayo ni ile naa;OLUWA ko ni fi i le awon ota re lowo.Eru ba Dafidi nitori pe Saulu n wa ona lati pa a.Dafidi n gbe asale Sifi ni Horesi. Ona atigun oke Heresi ni Gideoni gba nigba ti o n ti oju ogun pada bo. Imele maa n fa osi,sugbon eni ti o ba tepa mose yoo di oloro.Oro to doju ru di ti oloro, aye a dehin.
Tí ẹ bá jẹ́ ti Kristi, a jẹ́ pé ẹ jẹ́ irú-ọmọ Abrahamu, ẹ sì di ajogún ìlérí. Wọ́n so ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ mọ́ ọn lẹ́sẹ̀,wọ́n ti ọrùn rẹ̀ bọ irin,Penina, orogún Hana, a máa fín in níràn gidigidi, kí ó baà lè mú un bínú, nítorí pé OLUWA kò fún un ní ọmọ bí. Títí lae ni ó ń ranti majẹmu rẹ̀,ó ranti àṣẹ tí ó pa fún ẹgbẹẹgbẹrun ìran,Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA!Wọn kò mọ ọ̀nà alaafia.“Ọpọlọpọ èso ni ẹ óo máa gbìn sinu oko yín, ṣugbọn díẹ̀ ni ẹ óo máa rí ká, nítorí eṣú ni yóo máa jẹ wọ́n. Wò ó, OLUWA yóo fi àjàkálẹ̀ àrùn ṣe àwọn eniyan rẹ, ati àwọn ọmọ rẹ, ati àwọn aya rẹ ati gbogbo ohun tí o ní. Resisting-while-being-pulled is the proper behavior for a bride; if she is pulled and she does not resist, something is the matter with her.
Ti e ba je ti Kristi, a je pe e je iru-omo Abrahamu, e si di ajogun ileri. Won so sekeseke mo on lese,won ti orun re bo irin,Penina, orogun Hana, a maa fin in niran gidigidi, ki o baa le mu un binu, nitori pe OLUWA ko fun un ni omo bi. Titi lae ni o n ranti majemu re,o ranti ase ti o pa fun egbeegberun iran,Ninu isoro nla ni mo n ke pe o, OLUWA!Won ko mo ona alaafia.“Opolopo eso ni e oo maa gbin sinu oko yin, sugbon die ni e oo maa ri ka, nitori esu ni yoo maa je won. Wo o, OLUWA yoo fi ajakale arun se awon eniyan re, ati awon omo re, ati awon aya re ati gbogbo ohun ti o ni. Resisting-while-being-pulled is the proper behavior for a bride; if she is pulled and she does not resist, something is the matter with her.
Bojúwo ilẹ̀ láti ibùgbé mímọ́ rẹ lọ́run, kí o sì bukun Israẹli, àwọn eniyan rẹ, ati ilẹ̀ tí o ti fi fún wa gẹ́gẹ́ bí o ti ṣèlérí fún àwọn baba wa, ilẹ̀ tí ó kún fún wàrà ati oyin.’Jesu sọ fún wọn pé, “Ẹ máa tẹ̀lé mi, kì í ṣe ẹja ni ẹ óo máa pamọ́, eniyan ni ẹ óo máa fà wá.” Nígbà tí àwọn àgbààgbà péjọ tán, àwọn ọmọ Lefi gbé àpótí náà. Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa;kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára;Nítorí ó ń retí ìlú tí ó ní ìpìlẹ̀, tí ó jẹ́ pé Ọlọrun ni ó ṣe ètò rẹ̀ tí ó sì kọ́ ọ.ṣugbọn òun alára wọ inú ijù lọ ní ìrìn odidi ọjọ́ kan kí ó tó dúró. Ó bá jókòó lábẹ́ ìbòòji igi kan, ó wo ara rẹ̀ bíi kí òun kú. Ó sì gbadura sí OLUWA pé, “OLUWA, ó tó gẹ́ẹ́ báyìí! Kúkú pa mí. Kí ni mo fi sàn ju àwọn baba mi lọ?” Joabu ni balogun àwọn ọmọ ogun ní Israẹli. Bẹnaya ọmọ Jehoiada sì ní olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba. Egungun rẹ̀ dàbí ọ̀pá idẹ,ọwọ́ ati ẹsẹ̀ rẹ̀ rí bí irin.The moth (that) tries to put out the barbecue fire: the meat becomes more plentiful.
Bojuwo ile lati ibugbe mimo re lorun, ki o si bukun Israeli, awon eniyan re, ati ile ti o ti fi fun wa gege bi o ti seleri fun awon baba wa, ile ti o kun fun wara ati oyin.’Jesu so fun won pe, “E maa tele mi, ki i se eja ni e oo maa pamo, eniyan ni e oo maa fa wa.” Nigba ti awon agbaagba pejo tan, awon omo Lefi gbe apoti naa. Ki Olorun oo saanu wa, ki o bukun wa;ki oju re tan imole si wa lara;Nitori o n reti ilu ti o ni ipile, ti o je pe Olorun ni o se eto re ti o si ko o.sugbon oun alara wo inu iju lo ni irin odidi ojo kan ki o to duro. O ba jokoo labe ibooji igi kan, o wo ara re bii ki oun ku. O si gbadura si OLUWA pe, “OLUWA, o to gee bayii! Kuku pa mi. Ki ni mo fi san ju awon baba mi lo?” Joabu ni balogun awon omo ogun ni Israeli. Benaya omo Jehoiada si ni olori awon eso oba. Egungun re dabi opa ide,owo ati ese re ri bi irin.The moth (that) tries to put out the barbecue fire: the meat becomes more plentiful.
A person who foolishly attempts dangerous tasks courts destruction. This is a variant of Àfòpina tó ní òun ó pa fìtílà . . .
A person who foolishly attempts dangerous tasks courts destruction. This is a variant of Afopina to ni oun o pa fitila . . .
Àwọn ìlú ati àwọn ìletò wọnyi ni ìpín tí ó kan ẹ̀yà Dani gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn. Bilidadi ará Ṣuha dáhùn pé,Alufaa yóo fi ọ̀kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, yóo fi ikeji rú ẹbọ sísun láti ṣe ètùtù fún un nítorí pé ó ti ṣẹ̀ nípa fífi ara kan òkú; yóo sì ya orí rẹ̀ sí mímọ́ ní ọjọ́ náà. Nítorí pé ó tẹ́tí sí mi,nítorí náà, n óo máa ké pè éníwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.Gbogbo àwọn aṣẹ́wó ọkunrin tí wọ́n wà ní ojúbọ àwọn oriṣa káàkiri ní ilẹ̀ Juda, ni Asa lé jáde kúrò ni ilẹ̀ náà; ó sì kó gbogbo àwọn oriṣa tí àwọn baba ńlá rẹ̀ ti ṣe dànù. Ọ̀ràn tí ò sunwọ̀n, konko ǹṣojú.
Awon ilu ati awon ileto wonyi ni ipin ti o kan eya Dani gege bi iye idile won. Bilidadi ara Suha dahun pe,Alufaa yoo fi okan ru ebo imukuro ese, yoo fi ikeji ru ebo sisun lati se etutu fun un nitori pe o ti se nipa fifi ara kan oku; yoo si ya ori re si mimo ni ojo naa. Nitori pe o teti si mi,nitori naa, n oo maa ke pe eniwon igba ti mo ba wa laaye.Gbogbo awon asewo okunrin ti won wa ni ojubo awon orisa kaakiri ni ile Juda, ni Asa le jade kuro ni ile naa; o si ko gbogbo awon orisa ti awon baba nla re ti se danu. Oran ti o sunwon, konko nsoju.
Ó ṣe! Fún àwọn aboyún ati fún àwọn tí wọn bá ń tọ́ ọmọ lọ́wọ́ ní ọjọ́ náà. Ṣugbọn èmi dàbí igi olifi tútùtí ń dàgbà ninu ilé OLUWA,mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Ọlọrun tí kì í yẹ̀, lae ati laelae.Ṣugbọn ní ọdún keje, o gbọdọ̀ fi oko náà sílẹ̀ kí ó sinmi, kí àwọn talaka ninu yín náà lè rí oúnjẹ jẹ, kí àwọn ẹranko sì jẹ ninu èyí tí àwọn talaka bá jẹ kù. Bẹ́ẹ̀ ni o gbọdọ̀ ṣe ọgbà àjàrà rẹ, ati ọgbà olifi rẹ pẹlu. The meandering person knows where he is headed.
O se! Fun awon aboyun ati fun awon ti won ba n to omo lowo ni ojo naa. Sugbon emi dabi igi olifi tututi n dagba ninu ile OLUWA,mo gbekele ife Olorun ti ki i ye, lae ati laelae.Sugbon ni odun keje, o gbodo fi oko naa sile ki o sinmi, ki awon talaka ninu yin naa le ri ounje je, ki awon eranko si je ninu eyi ti awon talaka ba je ku. Bee ni o gbodo se ogba ajara re, ati ogba olifi re pelu. The meandering person knows where he is headed.
Maaka, Iyawo Makiri, bí ọmọ meji: Pereṣi ati Ṣereṣi. Ṣereṣi ni ó bí Ulamu ati Rakemu; Aguntan kò jẹ́ tẹ̀lé àlejò, sísá ni wọ́n máa ń sá fún un, nítorí wọn kò mọ ohùn àlejò.”Jẹ́ kí àwọn eniyan túká, kí wọn lè lọ sí àwọn abà ati abúlé tí ó wà yíká láti ra oúnjẹ fún ara wọn.”Ó kú, wọ́n sì sin ín sinu ibojì àwọn ọba ní ìlú Dafidi, Jotamu, ọmọ rẹ̀, sì jọba lẹ́yìn rẹ̀. Ṣugbọn mo tún ń ranti nǹkankan,mo sì ní ìrètí.Bẹ́ẹ̀ ni ẹ má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni pè yín ní ‘Ọ̀gá,’ nítorí ọ̀gá kanṣoṣo ni ẹ ní, òun ni Mesaya. Mose wọ inú ìkùukùu náà lọ, ó gun orí òkè náà, ó sì wà níbẹ̀ fún ogoji ọjọ́, tọ̀sán-tòru. Ọlọrun mi, Ọlọrun mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀,tí o fi jìnnà sí mi, tí o kò gbọ́ igbe mi,kí o sì ràn mí lọ́wọ́?Ẹ̀yin tí ẹ bẹ̀rù OLUWA, ẹ máa yìn ín!Ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, ẹ fi ògo fún un,ẹ dúró tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ níwájú rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ọmọ Israẹli!Wọ́n rán àwọn amí láti lọ wo Bẹtẹli. (Lusi ni orúkọ ìlú náà tẹ́lẹ̀.) Ẹ̀sọ̀ ẹ̀sọ̀ la fi ńlá ọbẹ̀ tó gbóná.
Maaka, Iyawo Makiri, bi omo meji: Peresi ati Seresi. Seresi ni o bi Ulamu ati Rakemu; Aguntan ko je tele alejo, sisa ni won maa n sa fun un, nitori won ko mo ohun alejo.”Je ki awon eniyan tuka, ki won le lo si awon aba ati abule ti o wa yika lati ra ounje fun ara won.”O ku, won si sin in sinu iboji awon oba ni ilu Dafidi, Jotamu, omo re, si joba leyin re. Sugbon mo tun n ranti nnkankan,mo si ni ireti.Bee ni e ma je ki enikeni pe yin ni ‘Oga,’ nitori oga kansoso ni e ni, oun ni Mesaya. Mose wo inu ikuukuu naa lo, o gun ori oke naa, o si wa nibe fun ogoji ojo, tosan-toru. Olorun mi, Olorun mi, ki lo de ti o fi ko mi sile,ti o fi jinna si mi, ti o ko gbo igbe mi,ki o si ran mi lowo?Eyin ti e beru OLUWA, e maa yin in!Eyin omo Jakobu, e fi ogo fun un,e duro towotowo niwaju re, gbogbo eyin omo Israeli!Won ran awon ami lati lo wo Beteli. (Lusi ni oruko ilu naa tele.) Eso eso la fi nla obe to gbona.
Ẹni tí ń fi tọkàntọkàn ṣiṣẹ́ ni yóo máa jẹ́ olórí,ṣugbọn ọ̀lẹ ni a óo máa mú ṣiṣẹ́ tipátipá.Joṣua, ọmọ Nuni, bá pe àwọn alufaa, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gbé Àpótí Majẹmu, kí meje ninu yín sì mú fèrè ogun tí wọ́n fi ìwo àgbò ṣe lọ́wọ́ níwájú Àpótí Majẹmu OLUWA.” Kí ó má gbẹ́kẹ̀lé òfo,kí ó má máa tan ara rẹ̀ jẹ,nítorí òfo ni yóo jẹ́ èrè rẹ̀.Ṣugbọn bí ẹ bá rọ́ àlá náà, tí ẹ sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀, ẹ óo gba ẹ̀bùn, ìdálọ́lá ati ẹ̀yẹ ńlá, nítorí náà ẹ rọ́ àlá náà fún mi, kí ẹ sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀.”Gbogbo ohun èlò ilé Ọlọrun ni Ahasi gé wẹ́wẹ́, ó sì ti ìlẹ̀kùn ibẹ̀; ó wá tẹ́ pẹpẹ oriṣa káàkiri Jerusalẹmu. bí o bá kígbe tí o tọrọ òye tí ó jinlẹ̀,tí o gbóhùn sókè tí o bèèrè ìmọ̀,pẹlu ìrànlọ́wọ́ àwọn ọkunrin mejila náà, wọ́n kọ orúkọ gbogbo àwọn ọmọ Israẹli sílẹ̀, láti ẹni ogún ọdún sókè, ní agbo-ilé agbo-ilé, ati ní ìdílé-ìdílé. Ẹbọ jíjẹ kì í pa igún.
Eni ti n fi tokantokan sise ni yoo maa je olori,sugbon ole ni a oo maa mu sise tipatipa.Josua, omo Nuni, ba pe awon alufaa, o so fun won pe, “E gbe Apoti Majemu, ki meje ninu yin si mu fere ogun ti won fi iwo agbo se lowo niwaju Apoti Majemu OLUWA.” Ki o ma gbekele ofo,ki o ma maa tan ara re je,nitori ofo ni yoo je ere re.Sugbon bi e ba ro ala naa, ti e si so itumo re, e oo gba ebun, idalola ati eye nla, nitori naa e ro ala naa fun mi, ki e si so itumo re.”Gbogbo ohun elo ile Olorun ni Ahasi ge wewe, o si ti ilekun ibe; o wa te pepe orisa kaakiri Jerusalemu. bi o ba kigbe ti o toro oye ti o jinle,ti o gbohun soke ti o beere imo,pelu iranlowo awon okunrin mejila naa, won ko oruko gbogbo awon omo Israeli sile, lati eni ogun odun soke, ni agbo-ile agbo-ile, ati ni idile-idile. Ebo jije ki i pa igun.
Hana dá a lóhùn, pé, “Rárá o, oluwa mi, n kò fẹnu kan ọtí waini tabi ọtí líle. Ìbànújẹ́ ló bá mi, tóbẹ́ẹ̀ tí mo fi ń gbadura, tí mo sì ń tú ọkàn mi jáde fún OLUWA. Pa mí mọ́ bí ẹyin ojú,dáàbò bò mí lábẹ́ òjìji ìyẹ́ rẹ;Ṣeba ati Dedani ati àwọn oníṣòwò Taṣiṣi, ati àwọn ìlú agbègbè wọn yóo bi ọ́ pé, ‘Ṣé o wá kó ìkógun ni, ṣé o kó àwọn ọmọ ogun rẹ jọ láti wá kó ẹrú, fadaka ati wúrà, ati mààlúù, ọrọ̀ ati ọpọlọpọ ìkógun?’ ”Whoever has a job should not malinger; if Providence smiles on one one can hardly fail.
Hana da a lohun, pe, “Rara o, oluwa mi, n ko fenu kan oti waini tabi oti lile. Ibanuje lo ba mi, tobee ti mo fi n gbadura, ti mo si n tu okan mi jade fun OLUWA. Pa mi mo bi eyin oju,daabo bo mi labe ojiji iye re;Seba ati Dedani ati awon onisowo Tasisi, ati awon ilu agbegbe won yoo bi o pe, ‘Se o wa ko ikogun ni, se o ko awon omo ogun re jo lati wa ko eru, fadaka ati wura, ati maaluu, oro ati opolopo ikogun?’ ”Whoever has a job should not malinger; if Providence smiles on one one can hardly fail.
Diligence in one's pursuit will certainly result in prosperity. Compare Ẹni tí a bá ḿbá ṣiṣẹ́ . . .
Diligence in one's pursuit will certainly result in prosperity. Compare Eni ti a ba mba sise . . .
(láti ìgbà èwe rẹ̀ ni mo ti ń ṣe bíi baba fún un,tí mo sì ń tọ́jú rẹ̀ láti inú ìyá rẹ̀); Ní àkókò náà Jesu ń la oko ọkà kan kọjá ní Ọjọ́ Ìsinmi àwọn Juu. Ebi ń pa àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ni wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí já ọkà, wọ́n ń jẹ ẹ́. 7. Ẹni tí ô ṣe ẹ̀yí ni Ọba Olùmọ
(lati igba ewe re ni mo ti n se bii baba fun un,ti mo si n toju re lati inu iya re); Ni akoko naa Jesu n la oko oka kan koja ni Ojo Isinmi awon Juu. Ebi n pa awon omo-eyin re, ni won ba bere si ja oka, won n je e. 7. Eni ti o se eyi ni Oba Olumo
ohun tí ô pamọ àti ohun tí ô hàn,
ohun ti o pamo ati ohun ti o han,
A lagbára, Aláàánú jùlọ,
A lagbara, Alaaanu julo,
8. Ẹni tí ô ṣe ohun gbogbo tí ÒÔ
8. Eni ti o se ohun gbogbo ti OO
dá ní dáradára, tí OÔ sì pilẹ̀ ìsẹ̀dá
da ni daradara, ti OO si pile iseda
ẹ̀nìyàn láti inú amọ.
eniyan lati inu amo.
9, Lẹ̀hhn náà O ṣẹ̀dá. àwọn
9, Lehhn naa O seda. awon
arọmọdọmọ rẹ̀ láti ara ohun tí ô
aromodomo re lati ara ohun ti o
Jáde nínú omi lọgbọlọgbọ.
Jade ninu omi logbologbo.
10. Lẹ̀hín náà ÒÔ dá a ní àdápé, O
10. Lehin naa OO da a ni adape, O
sì mí ẹémí Rẹ̀ sí i; O sì fún yín ní
si mi eemi Re si i; O si fun yin ni
ìgbọràn, ìríran àti ọkàn. Dbṣfẹ̀ sì ni
igboran, iriran ati okan. Dbsfe si ni
ìdúpẹ yín.
idupe yin.
11. Wọn sì wí pé, 'Kínla! Njẹ bí
11. Won si wi pe, 'Kinla! Nje bi
a bá ti parẹ sínú ilẹ̀, a o tún padà
a ba ti pare sinu ile, a o tun pada
di ẹ̀dá tuntun ni bí?" Kíyẹésí i,
di eda tuntun ni bi?" Kiyeesi i,
wọn. jẹ aláìnígbàgbọ sí ìbápàdé
won. je alainigbagbo si ibapade
Olúwa wọn.
Oluwa won.
12. Sọ pé, 'Malaika ikú tí a ti fi
12. So pe, 'Malaika iku ti a ti fi
yin lé lọwọ yòò pa yín: Lẹ̀hìn náà
yin le lowo yoo pa yin: Lehin naa
òdọ Olúwa yín ni a o mú yín
odo Oluwa yin ni a o mu yin
padà wa.
pada wa.
ÌDÁ 2
IDA 2
13. Tò bá ṣe pé ìwọ lò rí i nígbà tí
13. To ba se pe iwo lo ri i nigba ti
àwọn ẹlẹ̀ṣẹ̀ yôò sorí kodò níwájú
awon elese yoo sori kodo niwaju
Olúwa wọn tí wọn yòò máa sọ
Oluwa won ti won yoo maa so
pé, 'Olúwa wa àwá ti ri, a sì ti
pe, 'Oluwa wa awa ti ri, a si ti
gbọ, nítorí náà dá wa padà, kí 4
gbo, nitori naa da wa pada, ki 4
lẹ̀ lọ ṣe iṣẹ rere.. Dájúdájú àwa ti
le lo se ise rere.. Dajudaju awa ti
mọ àmòọdájú."
mo amoodaju."
14. Tô bá ṣe pé Àwá fẹ ni,
14. To ba se pe Awa fe ni,
olúkúlùkù ẹ̀mí ni À bá fún ní
olukuluku emi ni A ba fun ni
ìtọsọnà tirẹ̀, ṣùgbọn ọrọ Mi ti di
itosona tire, sugbon oro Mi ti di
Ìloro rẹ̀ kọjú sí gbọ̀ngàn òde, àwòrán ọ̀pẹ wà lára àtẹ́rígbà rẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ kinni keji, àtẹ̀gùn rẹ̀ sì ní ìgbésẹ̀ mẹjọ.Gbogbo àfonífojì ni a óo ru sókè,a óo sì sọ àwọn òkè ńlá ati òkè kéékèèké di pẹ̀tẹ́lẹ̀:Gbogbo ọ̀nà tí ó wọ́ ni yóo di títọ́,ọ̀nà gbágun-gbàgun yóo sì di títẹ́jú.“Ó dára, mo gbọ́, ẹ wá kọ́ mi,ẹ ṣàlàyé ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀ fún mi;n óo sì dákẹ́ n óo tẹ́tí sílẹ̀.Àwọn ni baba ńlá àwọn tí wọn ń gbé etí òkun ati àwọn erékùṣù, tí wọ́n tàn káàkiri. Àwọn ọmọ Jafẹti nìwọ̀nyí ní ìdílé ìdílé wọn, olukuluku ní agbègbè tirẹ̀. Oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè ni wọ́n, wọ́n sì ń sọ oríṣìíríṣìí èdè.Bí iná tíí jó igbó,àní, bí ọwọ́ iná sì ṣe ń jó òkè kanlẹ̀,OLUWA gbọ́ ohùn àwọn ọmọ Israẹli, ó sì ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ṣẹgun àwọn ará Kenaani. Wọ́n run àwọn ati àwọn ìlú wọn patapata. Àwọn ọmọ Israẹli sì sọ ibẹ̀ ní Horima.ó sọ wá di alààyè pẹlu Kristi nígbà tí a ti di òkú ninu ìwàkíwà wa. Oore-ọ̀fẹ́ ni a fi gbà yín là. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Eseri ọmọ Jeṣua, aláṣẹ Misipa, náà ṣe àtúnṣe apá kan lára ibi ihamọra ní ibi igun odi.Ọdọmọkunrin náà dá a lóhùn pé, “Ohunkohun tí ọkàn rẹ bá fẹ́ ni kí o ṣe. Mo wà lẹ́yìn rẹ, bí ọkàn rẹ ti rí ni tèmi náà rí.”Atúniká ti gbógun tì ọ́, ìwọ Ninefe.Yan eniyan ṣọ́ ibi ààbò;máa ṣọ́nà, di àmùrè rẹ,kí o sì múra ogun.Nítorí Ọmọ-Eniyan ń lọ gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ nípa rẹ̀, ṣugbọn ẹni tí yóo fi Ọmọ-Eniyan lé àwọn ọ̀tá lọ́wọ́ gbé! Ìbá sàn fún un bí a kò bá bí i.”Lẹ́yìn náà, mo bá àwọn alufaa ati gbogbo àwọn eniyan náà sọ̀rọ̀, mo ní, “OLUWA sọ pé ẹ kò gbọdọ̀ fetí sí ọ̀rọ̀ àwọn wolii yín tí wọn ń wí fun yín pé wọn kò ní pẹ́ kó àwọn ohun èlò ilé èmi OLUWA pada wá láti Babiloni. Àsọtẹ́lẹ̀ èké ni wọ́n ń sọ fun yín. Àwọn eniyan tí wọ́n wà pẹlu Jesu nígbà tí ó fi pe Lasaru jáde kúrò ninu ibojì, tí ó jí i dìde kúrò ninu òkú, ń ròyìn ohun tí wọ́n rí. Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli kúrò ní Kadeṣi, wọ́n wá sí òkè Hori Nítorí bí Jona ti di àmì fún àwọn ará Ninefe, bẹ́ẹ̀ gan-an ni Ọmọ-Eniyan yóo jẹ́ àmì fún ìran yìí. Kò sí ọba ní ilẹ̀ Edomu. Adelé ọba kan ní ń ṣàkóso ilẹ̀ náà.OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: Ìdí nìyí ti a fi ń pe ilẹ̀ náà ní, “Ilẹ̀ ẹ̀jẹ̀” títí di òní olónìí. “Bí arakunrin rẹ bá di aláìní tóbẹ́ẹ̀ tí kò lè bọ́ ara rẹ̀ mọ́, o níláti máa bọ́ ọ, kí ó sì máa gbé ọ̀dọ̀ rẹ, gẹ́gẹ́ bí àlejò ati àjèjì. Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé agbowó-odè yìí lọ sí ilé rẹ̀ pẹlu ọkàn ìdáláre ju èyí Farisi lọ. Nítorí ẹni tí ó bá gbé ara rẹ̀ ga ni a óo rẹ̀ sílẹ̀; ẹni tí ó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ ni a óo gbé ga.” Ṣugbọn a kó àwọn ẹran ọ̀sìn wọn, ati àwọn ohun tí a rí ninu ìlú wọn bí ìkógun.OLUWA, da ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ bò wọ́n,jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ pé aláìlágbára eniyan ni àwọn.“Ẹ kọ́ ẹ̀kọ́ lára igi ọ̀pọ̀tọ́. Nígbà tí ẹ̀ka rẹ̀ bá ṣẹ̀ṣẹ̀ yọ, tí ó rú ewé, ẹ mọ̀ pé àkókò ẹ̀ẹ̀rùn súnmọ́ ìtòsí. If a child is an adept ayò player, one defeats him with single seeds.
Iloro re koju si gbongan ode, aworan ope wa lara aterigba re legbee kinni keji, ategun re si ni igbese mejo.Gbogbo afonifoji ni a oo ru soke,a oo si so awon oke nla ati oke keekeeke di petele:Gbogbo ona ti o wo ni yoo di tito,ona gbagun-gbagun yoo si di titeju.“O dara, mo gbo, e wa ko mi,e salaye ese ti mo se fun mi;n oo si dake n oo teti sile.Awon ni baba nla awon ti won n gbe eti okun ati awon erekusu, ti won tan kaakiri. Awon omo Jafeti niwonyi ni idile idile won, olukuluku ni agbegbe tire. Orisiirisii orile-ede ni won, won si n so orisiirisii ede.Bi ina tii jo igbo,ani, bi owo ina si se n jo oke kanle,OLUWA gbo ohun awon omo Israeli, o si ran won lowo lati segun awon ara Kenaani. Won run awon ati awon ilu won patapata. Awon omo Israeli si so ibe ni Horima.o so wa di alaaye pelu Kristi nigba ti a ti di oku ninu iwakiwa wa. Oore-ofe ni a fi gba yin la. Leyin re ni Eseri omo Jesua, alase Misipa, naa se atunse apa kan lara ibi ihamora ni ibi igun odi.Odomokunrin naa da a lohun pe, “Ohunkohun ti okan re ba fe ni ki o se. Mo wa leyin re, bi okan re ti ri ni temi naa ri.”Atunika ti gbogun ti o, iwo Ninefe.Yan eniyan so ibi aabo;maa sona, di amure re,ki o si mura ogun.Nitori Omo-Eniyan n lo gege bi akosile nipa re, sugbon eni ti yoo fi Omo-Eniyan le awon ota lowo gbe! Iba san fun un bi a ko ba bi i.”Leyin naa, mo ba awon alufaa ati gbogbo awon eniyan naa soro, mo ni, “OLUWA so pe e ko gbodo feti si oro awon wolii yin ti won n wi fun yin pe won ko ni pe ko awon ohun elo ile emi OLUWA pada wa lati Babiloni. Asotele eke ni won n so fun yin. Awon eniyan ti won wa pelu Jesu nigba ti o fi pe Lasaru jade kuro ninu iboji, ti o ji i dide kuro ninu oku, n royin ohun ti won ri. Gbogbo awon omo Israeli kuro ni Kadesi, won wa si oke Hori Nitori bi Jona ti di ami fun awon ara Ninefe, bee gan-an ni Omo-Eniyan yoo je ami fun iran yii. Ko si oba ni ile Edomu. Adele oba kan ni n sakoso ile naa.OLUWA tun ba mi soro, o ni: Idi niyi ti a fi n pe ile naa ni, “Ile eje” titi di oni olonii. “Bi arakunrin re ba di alaini tobee ti ko le bo ara re mo, o nilati maa bo o, ki o si maa gbe odo re, gege bi alejo ati ajeji. Mo fe ki e mo pe agbowo-ode yii lo si ile re pelu okan idalare ju eyi Farisi lo. Nitori eni ti o ba gbe ara re ga ni a oo re sile; eni ti o ba re ara re sile ni a oo gbe ga.” Sugbon a ko awon eran osin won, ati awon ohun ti a ri ninu ilu won bi ikogun.OLUWA, da erujeje bo won,je ki awon orile-ede mo pe alailagbara eniyan ni awon.“E ko eko lara igi opoto. Nigba ti eka re ba sese yo, ti o ru ewe, e mo pe akoko eerun sunmo itosi. If a child is an adept ayo player, one defeats him with single seeds.
Àwọn ará Juda bẹ̀rẹ̀ sí kọrin pé,“Agbára àwa tí à ń ṣe iṣẹ́ ń dín kù,iṣẹ́ sì tún pọ̀ nílẹ̀;ǹjẹ́ a ó lè mọ odi náà mọ́ báyìí?”Nígbà náà ni mo sọ pé,‘A ti ta mí nù kúrò níwájú rẹ;báwo ni n óo ṣe tún rí tẹmpili mímọ́ rẹ?’Ṣugbọn ọkàn ẹ̀yin eniyan wọnyi le, ọlọ̀tẹ̀ sì ni yín.Ẹ ti yapa, ẹ sì ti ṣáko lọ.Bí a ti ní oríṣìíríṣìí ẹ̀bùn gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti pín oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kí á lò wọ́n. Bí ẹnìkan bá ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀, kí ó lò ó gẹ́gẹ́ bí igbagbọ rẹ̀ ti mọ. Arabinrin mi dàbí ọgbà tí a ti ti ìlẹ̀kùn rẹ̀.Ọgbà tí a tì ni iyawo mi;àní orísun omi tí a tì ni ọ́.Ọba dáhùn pé, “Ohunkohun tí ẹ bá ní kí n ṣe náà ni n óo ṣe.” Ọba bá dúró ní ẹnu ibodè, bí àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí ń tò kọjá lọ ní ọgọọgọrun-un (100) ati ẹgbẹẹgbẹrun (1,000). Ẹ pa ara yín mọ́ ninu ìfẹ́ Ọlọrun. Ẹ máa retí ìyè ainipẹkun tí Oluwa wa Jesu Kristi yóo fun yín ninu àánú rẹ̀.Bí wọ́n bá gbọ́ràn, tí wọ́n sì sìn ín,wọn yóo lo ọjọ́ ayé wọn pẹlu ìdẹ̀rùn,wọn yóo ṣe ọ̀pọ̀ ọdún ninu ìgbádùn.Fà mí mọ́ra, jẹ́ kí á ṣe kíá,ọba ti mú mi wọ yàrá rẹ̀.Inú wa yóo máa dùn, a óo sì máa yọ̀ nítorí rẹa óo gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí waini lọ;abájọ tí gbogbo àwọn obinrin ṣe fẹ́ràn rẹ!bí wọn bá ṣe àtúnṣe láàrin ara wọn
Awon ara Juda bere si korin pe,“Agbara awa ti a n se ise n din ku,ise si tun po nile;nje a o le mo odi naa mo bayii?”Nigba naa ni mo so pe,‘A ti ta mi nu kuro niwaju re;bawo ni n oo se tun ri tempili mimo re?’Sugbon okan eyin eniyan wonyi le, olote si ni yin.E ti yapa, e si ti sako lo.Bi a ti ni orisiirisii ebun gege bi Olorun ti pin oore-ofe re, bee ni ki a lo won. Bi enikan ba ni ebun isotele, ki o lo o gege bi igbagbo re ti mo. Arabinrin mi dabi ogba ti a ti ti ilekun re.Ogba ti a ti ni iyawo mi;ani orisun omi ti a ti ni o.Oba dahun pe, “Ohunkohun ti e ba ni ki n se naa ni n oo se.” Oba ba duro ni enu ibode, bi awon omo ogun re ti n to koja lo ni ogoogorun-un (100) ati egbeegberun (1,000). E pa ara yin mo ninu ife Olorun. E maa reti iye ainipekun ti Oluwa wa Jesu Kristi yoo fun yin ninu aanu re.Bi won ba gboran, ti won si sin in,won yoo lo ojo aye won pelu iderun,won yoo se opo odun ninu igbadun.Fa mi mora, je ki a se kia,oba ti mu mi wo yara re.Inu wa yoo maa dun, a oo si maa yo nitori rea oo gbe ife re ga ju oti waini lo;abajo ti gbogbo awon obinrin se feran re!bi won ba se atunse laarin ara won
ní ìtùbí-ìnùbí; (ṣíṣe) àtúnṣe l0 sì
ni itubi-inubi; (sise) atunse l0 si
dára jùlọ. Àwọn ẹ̀nìyàn sì máa n tẹ̀
dara julo. Awon eniyan si maa n te
sí ìwà ojúkòkòrò. Bí ẹ bá ṣe rere tí
si iwa ojukokoro. Bi e ba se rere ti
ẹ sì bẹ̀rù Allah; dájúdájú Allah mọ
e si beru Allah; dajudaju Allah mo
ohun tí ẹ fì ṣe.
ohun ti e fi se.
130. Ẹyin kì yòò le ní agbára láti
130. Eyin ki yoo le ni agbara lati
ṣe ẹ̀tọ (kíkún) láàrin. àwọn
se eto (kikun) laarin. awon
obìnrin, bí ô ti wù kí ẹ nífẹ̀ẹ sí ṣíṣe
obinrin, bi o ti wu ki e nifee si sise
bẹ̀ẹ̀ to, ṣùgbọn ẹ má ṣe fi gbogbo
bee to, sugbon e ma se fi gbogbo
pọ sí ẹ̀dò ẹnìkan; kí ẹ wá pa
po si edo enikan; ki e wa pa
ẹnìkejì tì gẹgẹ bí ohun ìkọtì,
enikeji ti gege bi ohun ikoti,
ṣùgbọn tí ẹ bá ṣe àtúnṣe, kí ẹ sì
sugbon ti e ba se atunse, ki e si
bẹ̀rù Allah, dájúdájú Allah ní
beru Allah, dajudaju Allah ni
Alaforíjìn, Aláàánú jùlọ.
Alaforijin, Alaaanu julo.
Allah yòò rọ oníkálùkù wọn lọrọ
Allah yoo ro onikaluku won loro
láti inú ọlá Rẹ̀. Allah sì jẹ Ọlọlá tò
lati inu ola Re. Allah si je Olola to
nh bẹ ní àwọn ọrun àti ayé.
nh be ni awon orun ati aye.
Dájúdájú À wa ti pàṣẹ fún àwọn tí
Dajudaju A wa ti pase fun awon ti
a fún ní Ìwé ṣíwájú yín àti ẹ̀yin náà
a fun ni Iwe siwaju yin ati eyin naa
pẹ̀lú láti máa bẹ̀rù Allah. Ṣùgbọn
pelu lati maa beru Allah. Sugbon
tí ẹ̀yin bá ṣe àìgbàgbọ, dájúdájú tí
ti eyin ba se aigbagbo, dajudaju ti
Allah ni ohun gbogbo tí n bẹ ni
Allah ni ohun gbogbo ti n be ni