diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ẹ̀yin dojú nǹkan délẹ̀,bí ẹni pé wọ́n rò pé amọ̀kòkò dàbí amọ̀!Ǹjẹ́ ohun tí a ṣe le sọ fún olùṣe pé“Òun kọ́ ló ṣe mí”?Ǹjẹ́ ìkòkò lè sọ nípa amọ̀kòkò pé,“kò mọ nǹkan”?
Eyin doju nnkan dele,bi eni pe won ro pe amokoko dabi amo!Nje ohun ti a se le so fun oluse pe“Oun ko lo se mi”?Nje ikoko le so nipa amokoko pe,“ko mo nnkan”?
( b ) Sọ àpẹẹrẹ tó fi hàn pé àwọn èèyàn ń kíyè sí ìfẹ́ tá à ń fi hàn .
( b ) So apeere to fi han pe awon eeyan n kiye si ife ta a n fi han .
Nínú fídíò náà , wàá rí bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lórílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì àti Palẹ́sínì kò ṣe gba ẹ̀mí kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà láyè láàárín wọn . ( wo abẹ́ ABOUT US > CONVENTIONS )
Ninu fidio naa , waa ri bi awon Elerii Jehofa to wa lorile - ede Isireli ati Palesini ko se gba emi keleyameya laye laaarin won . ( wo abe ABOUT US > CONVENTIONS )
Ọ̀gbẹ́ni Ted Turner tó dá ilé iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n CNN sílẹ̀ ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀ èèyàn kárí ayé , ó sì sọ ohun tó wú u lórí nípa wọn .
Ogbeni Ted Turner to da ile ise telifison CNN sile ti sise pelu opo eeyan kari aye , o si so ohun to wu u lori nipa won .
Ọ̀dọ̀ ẹni tó bá buwọ́ lu lẹ́tà la máa ń gbà pé lẹ́tà náà ti wá
Odo eni to ba buwo lu leta la maa n gba pe leta naa ti wa
haṣabaya
hasabaya
Ẹ wo àwọn ohun tí Jèhófà ti pèsè fún wa ná .
E wo awon ohun ti Jehofa ti pese fun wa na .
Àmọ́ nígbà tó yá , àwọn kan wá ń fi àdàpọ̀ wúrà àti nǹkan míì ṣe ayédèrú owó .
Amo nigba to ya , awon kan wa n fi adapo wura ati nnkan mii se ayederu owo .
Ó sì ṣe, nígbà tí àwọn angẹli náà padà kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ọ̀run, àwọn olùṣọ́-àgùntàn náà bá ara wọn sọ pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ tààrà sí Bẹtilẹhẹmu, kí á lè rí ohun tí ó ṣẹ̀, tí Olúwa fihàn fún wa.”
O si se, nigba ti awon angeli naa pada kuro lodo won lo si orun, awon oluso-aguntan naa ba ara won so pe, "E je ki a lo taara si Betilehemu, ki a le ri ohun ti o se, ti Oluwa fihan fun wa."
13 - 15 .
13 - 15 .
Àmọ́ nígbà tó yá mó wá bẹ̀rẹ̀ sí i rí i pé ó yẹ́ kí ń ní alábàákẹ́gbẹ́ kan nínú ayé mi .
Amo nigba to ya mo wa bere si i ri i pe o ye ki n ni alabaakegbe kan ninu aye mi .
▪ Ǹjẹ́ Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Ní Àjọṣe Tó Dán Mọ́rán Pẹ̀lú Jèhófà ?
# Nje O Da E Loju Pe O Ni Ajose To Dan Moran Pelu Jehofa ?
“Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì jẹ ohunkohun tí ó kú fúnra rẹ̀, tabi tí ẹranko burúkú fà ya, kí ẹni náà fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóo jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́, lẹ́yìn ìgbà náà ni yóo tó pada di mímọ́.
“Enikeni ti o ba si je ohunkohun ti o ku funra re, tabi ti eranko buruku fa ya, ki eni naa fo aso re, ki o si we, yoo je alaimo titi di irole, leyin igba naa ni yoo to pada di mimo.
Nígbà tí Jésù wà lórí ilẹ̀ ayé , ibi tó wàásù dé kò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀ , àkókò tó fi wàásù kò sì ju ọdún mẹ́ta àtààbọ̀ lọ .
Nigba ti Jesu wa lori ile aye , ibi to waasu de ko fi bee po , akoko to fi waasu ko si ju odun meta ataabo lo .
Ọ̀gbẹ́ni tá a mẹ́nu kàn níbẹ̀rẹ̀ àpilẹ̀kọ yìí kò kú nígbà tí ẹkùn ilẹ̀ Bengal tó fún ní ìdálẹ́kọ̀ọ́ gbéjà kò ó .
Ogbeni ta a menu kan nibere apileko yii ko ku nigba ti ekun ile Bengal to fun ni idalekoo gbeja ko o .
Àpọ́sítélì Mátíù : “ Lẹ́yìn tí a bí Jésù ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Jùdíà ní àwọn ọjọ́ Hẹ́rọ́dù Ọba , wò ó !
Apositeli Matiu : " Leyin ti a bi Jesu ni Betilehemu ti Judia ni awon ojo Herodu Oba , wo o !
bíì
bii
Bí wọ́n ti ń la àfonífojì Baka lọ,wọ́n ń sọ ọ́ di orísun omi;àkọ́rọ̀ òjò sì mú kí adágún omi kún ibẹ̀.Ọrẹ tirẹ̀ ni: àwo fadaka kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ aadoje (130) ṣekeli, abọ́ fadaka kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ aadọrin ṣekeli, ìwọ̀n tí wọn ń lò ní ibi mímọ́ ni wọ́n fi wọ̀n ọ́n. Àwo ati abọ́ náà kún fún ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi òróró pò fún ẹbọ ohun jíjẹ, N óo fi idà pa àwọn ọdọmọkunrin Oni ati ti Pibeseti; a óo sì kó àwọn obinrin wọn lọ sí ìgbèkùn. Kí arakunrin tí ó jẹ́ mẹ̀kúnnù kí ó yọ̀ nígbà tí Ọlọrun bá gbé e ga. Ẹni tí ó lágbára gba ilẹ̀,ẹni tí ó lọ́lá sì ń gbé inú rẹ̀.Wọ́n gbé àwọn òpó tí a fi òkúta ṣe ati àwọn ère Aṣerimu sí orí àwọn òkè ati sí abẹ́ àwọn igi tí wọ́n ní ìbòòji. Jehoṣafati, ọmọ Parua, ni alákòóso agbègbè Isakari. àwọn olórí àwọn ẹ̀yà Israẹli, tí wọ́n jẹ́ olórí ní ìdílé wọn, tí wọ́n sì wà pẹlu Mose nígbà tí ó ka àwọn eniyan Israẹli, Ó tún fi ọgọrun-un ìwọ̀n talẹnti fadaka lọ bẹ ọ̀kẹ́ marun-un (100,000) akọni lọ́wẹ̀ ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli. “ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí ó bá bá ẹranko lòpọ̀.’ “Gbogbo eniyan yóo dáhùn pé, ‘Amin.’Ṣé irú ààwẹ̀ tí mo yàn nìyí, ọjọ́ tí eniyan yóo rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ lásán?Ṣé kí eniyan lè doríkodò bíi koríko etí odò nìkan ni?Tabi kí ó lè jókòó lórí aṣọ ọ̀fọ̀ ati eérú nìkan?Ṣé èyí ni ẹ̀ ń pè ní ààwẹ̀, ati ọjọ́ tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ OLUWA?Afọ́jú àjànàkú, kò mọ igi, kò mọ èèyàn.
Bi won ti n la afonifoji Baka lo,won n so o di orisun omi;akoro ojo si mu ki adagun omi kun ibe.Ore tire ni: awo fadaka kan ti iwon re je aadoje (130) sekeli, abo fadaka kan ti iwon re je aadorin sekeli, iwon ti won n lo ni ibi mimo ni won fi won on. Awo ati abo naa kun fun iyefun kikunna ti a fi ororo po fun ebo ohun jije, N oo fi ida pa awon odomokunrin Oni ati ti Pibeseti; a oo si ko awon obinrin won lo si igbekun. Ki arakunrin ti o je mekunnu ki o yo nigba ti Olorun ba gbe e ga. Eni ti o lagbara gba ile,eni ti o lola si n gbe inu re.Won gbe awon opo ti a fi okuta se ati awon ere Aserimu si ori awon oke ati si abe awon igi ti won ni ibooji. Jehosafati, omo Parua, ni alakooso agbegbe Isakari. awon olori awon eya Israeli, ti won je olori ni idile won, ti won si wa pelu Mose nigba ti o ka awon eniyan Israeli, O tun fi ogorun-un iwon talenti fadaka lo be oke marun-un (100,000) akoni lowe ninu awon omo ogun Israeli. “ ‘Eni ifibu ni enikeni ti o ba ba eranko lopo.’ “Gbogbo eniyan yoo dahun pe, ‘Amin.’Se iru aawe ti mo yan niyi, ojo ti eniyan yoo re ara re sile lasan?Se ki eniyan le dorikodo bii koriko eti odo nikan ni?Tabi ki o le jokoo lori aso ofo ati eeru nikan?Se eyi ni e n pe ni aawe, ati ojo ti o se itewogba lodo OLUWA?Afoju ajanaku, ko mo igi, ko mo eeyan.
ÀRÀNMỌ́WÁJÚ NÍNÚ Ẹ̀KA ÈDÈ ÌKÁLẸ̀
ARANMOWAJU NINU EKA EDE IKALE
Mose bá wí ninu ara rẹ̀ pé, “N óo súnmọ́ kinní yìí, mo fẹ́ wo ohun ìyanu yìí, ìdí tí iná fi ń jó tí igbó kò sì fi jóná.”
Mose ba wi ninu ara re pe, "N oo sunmo kinni yii, mo fe wo ohun iyanu yii, idi ti ina fi n jo ti igbo ko si fi jona."
ẹ̀ka
eka
Ó ṣe kedere pé a lè máa fi Bíbélì wádìí ara wa ká lè mọ̀ bóyá a wà nínú ìgbàgbọ́ àti pé Jèhófà mọyì wa .
O se kedere pe a le maa fi Bibeli wadii ara wa ka le mo boya a wa ninu igbagbo ati pe Jehofa moyi wa .
Àwọn ọlọ́pàá yìí rò pé ohun tó ṣeyebíye ló wà nínú páálí márààrún táwọn kó !
Awon olopaa yii ro pe ohun to seyebiye lo wa ninu paali maraarun tawon ko !
Àbá kan ni pé ejò náà ṣe bẹ́ẹ̀ nípa fífi ara sọ̀rọ̀ tàbí fífi ara ṣàpèjúwe .
Aba kan ni pe ejo naa se bee nipa fifi ara soro tabi fifi ara sapejuwe .
Ǹjẹ́ inú ti bí ẹ rí torí ohun tí ará kan ṣe sí ẹ tàbí torí àǹfààní iṣẹ́ ìsìn kan tó bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́ ?
Nje inu ti bi e ri tori ohun ti ara kan se si e tabi tori anfaani ise isin kan to bo mo e lowo ?
[ Ìsọfúnni tá a pàfiyèsí sí ní ojú ìwé 4 ]
[ Isofunni ta a pafiyesi si ni oju iwe 4 ]
Déébè
Deebe
Sifi, Telemu, Bealoti,
Sifi, Telemu, Bealoti,
gbẹkẹ̀lé
gbekele
Jẹ ẹni tí òrọ ahọn rẹ̀ dá ṣákáṣaká
Je eni ti oro ahon re da sakasaka
[ Ìsọfúnni tá a pàfiyèsí sí ní ojú ìwé 20 ]
[ Isofunni ta a pafiyesi si ni oju iwe 20 ]
Àwọn ìdílé kan tó ń ṣiṣẹ́ oko tí wọ́n sì wà pa pọ̀ tímọ́tímọ́ nígbà kan rí kò tún fi bẹ́ẹ̀ wà pa pọ̀ mọ́ . ”
Awon idile kan to n sise oko ti won si wa pa po timotimo nigba kan ri ko tun fi bee wa pa po mo . ”
Ó fẹ́rẹ̀ tó àkókò Àjọ̀dún Àìwúkàrà tí à ń pè ní Àjọ̀dún Ìrékọjá.
O fere to akoko Ajodun Aiwukara ti a n pe ni Ajodun Irekoja.
Ǹjẹ́ wọ́n dúró lórí àdéhùn tí wọ́n bá Ọlọ́run ṣe ? — Ẹ́kísódù 19 : 3 - 8 .
Nje won duro lori adehun ti won ba Olorun se ? — Ekisodu 19 : 3 - 8 .
Ìwádìí náà fi hàn pé èèyàn méjì nínú mẹ́ta ló ka ara wọn sí ẹlẹ́sìn Kristi àmọ́ “ lọ́nà tó wù wọ́n . ”
Iwadii naa fi han pe eeyan meji ninu meta lo ka ara won si elesin Kristi amo “ lona to wu won . ”
“ ‘Ní gbogbo ìgbà ẹ̀jẹ́ ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀ yìí, kí abẹ kankan má ṣe kàn án ní orí. Ó gbọdọ̀ jẹ́ mímọ́ títí tí àkókò ìyàsọ́tọ̀ rẹ̀ sí yóò fi pé; ó gbọdọ̀ jẹ́ kí irun orí rẹ̀ gùn.
" 'Ni gbogbo igba eje iyasoto re yii, ki abe kankan ma se kan an ni ori. O gbodo je mimo titi ti akoko iyasoto re si yoo fi pe; o gbodo je ki irun ori re gun.
Ìgbà yẹn ni Jèhófà yóò tú agbo ọmọ ogun rẹ̀ sílẹ̀ láti pa gbogbo ìyókù ètò Sátánì lórí ilẹ̀ ayé run . — Ìṣí .
Igba yen ni Jehofa yoo tu agbo omo ogun re sile lati pa gbogbo iyoku eto Satani lori ile aye run . — Isi .
Ẹ̀ṣẹ̀ , 6 / 1
Ese , 6 / 1
Ábíṣáì rọra sọ fún Dáfídì pé : “ Jẹ́ kí n fi ọ̀kọ̀ gún un mọ́lẹ̀ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo péré , èmi kì yóò sì ṣe é sí i lẹ́ẹ̀mejì . ”
Abisai rora so fun Dafidi pe : " Je ki n fi oko gun un mole leekan soso pere , emi ki yoo si se e si i leemeji . "
“ ‘ Èmi fúnra mi mọ àwọn èrò tí mo ń rò nípa yín ní àmọ̀dunjú , ’ ni àsọjáde Jèhófà , ‘ àwọn èrò àlàáfíà , kì í ṣe ti ìyọnu àjálù , láti fún yín ní ọjọ́ ọ̀la kan àti ìrètí kan .
" ' Emi funra mi mo awon ero ti mo n ro nipa yin ni amodunju , ' ni asojade Jehofa , ' awon ero alaafia , ki i se ti iyonu ajalu , lati fun yin ni ojo ola kan ati ireti kan .
Àmọ́ , nígbà kan , àwùjọ àwọn èèyàn kan rìnrìn àjò láti àwọn ibi jíjìnnà kan nílùú Tuva lọ sílùú Kyzyl , tó jẹ́ olú ìlú Tuva fún ìdálẹ́kọ̀ọ́ kan .
Amo , nigba kan , awujo awon eeyan kan rinrin ajo lati awon ibi jijinna kan niluu Tuva lo siluu Kyzyl , to je olu ilu Tuva fun idalekoo kan .
Ìfẹ́ ńlá tí mo ní fún Jèhófà ló mú kí n fowó yìí ṣètọrẹ . ”
Ife nla ti mo ni fun Jehofa lo mu ki n fowo yii setore . ”
Nígbà tí Eberi di ẹni ọdún mẹrinlelọgbọn ni ó bí Pelegi.
Nigba ti Eberi di eni odun merinlelogbon ni o bi Pelegi.
Pọ́ọ̀lù kọ̀wé pé : “ [ Mo ] pàrọwà fún yín láti máa rìn lọ́nà tí ó yẹ . . . pẹ̀lú ìrẹ̀lẹ̀ pátápátá ti èrò inú àti ìwà tútù , pẹ̀lú ìpamọ́ra , ní fífaradà á fún ara yín lẹ́nì kìíní - kejì nínú ìfẹ́ , kí ẹ máa fi taratara sakun láti máa pa ìṣọ̀kanṣoṣo ẹ̀mí mọ́ nínú ìdè asonipọ̀ṣọ̀kan ti àlàáfíà . ” — Éfé .
Poolu kowe pe : “ [ Mo ] parowa fun yin lati maa rin lona ti o ye . . . pelu irele patapata ti ero inu ati iwa tutu , pelu ipamora , ni fifarada a fun ara yin leni kiini - keji ninu ife , ki e maa fi taratara sakun lati maa pa isokansoso emi mo ninu ide asoniposokan ti alaafia . ” — Efe .
Ògo táwọn ará Mídíà àtàwọn ará Páṣíà máa ń rí nígbà tí wọ́n bá ṣẹ́gun ṣe pàtàkì lójú wọn ju ẹrù tí wọ́n ń rí kó lójú ogun lọ .
Ogo tawon ara Midia atawon ara Pasia maa n ri nigba ti won ba segun se pataki loju won ju eru ti won n ri ko loju ogun lo .
Ǹjẹ́ nísin yìí bí ẹ̀yin yóò bá fi inú rere àti òtítọ́ bá olúwa mi lò, ẹ sọ fún mi, bí bẹ́ẹ̀ sì kọ́, ẹ sọ fún mi, kí ó le è mọ ọ̀nà tí èmi yóò yà sí
Nje nisin yii bi eyin yoo ba fi inu rere ati otito ba oluwa mi lo, e so fun mi, bi bee si ko, e so fun mi, ki o le e mo ona ti emi yoo ya si
Ohun náà ni pé , ìjọba tí Jèhófà gbé fún Jésù tó jẹ́ Mèsáyà àti “ àwọn ẹni mímọ́ ” tó máa wà pẹ̀lú rẹ̀ láti máa ṣàkóso látọ̀runwá ni “ ìjọba ” tí ibí yìí ń wí .
Ohun naa ni pe , ijoba ti Jehofa gbe fun Jesu to je Mesaya ati “ awon eni mimo ” to maa wa pelu re lati maa sakoso latorunwa ni “ ijoba ” ti ibi yii n wi .
Yóo dàbí ìgbà tí eniyan kórè ọkà lóko,tí ó kó ṣiiri ọkà kún apá.Tí àwọn kan tún wá ṣa ọkà yòókù,tí àwọn tí wọn kọ́ kórè ọkà gbàgbé ní àfonífojì Refaimu.
Yoo dabi igba ti eniyan kore oka loko,ti o ko siiri oka kun apa.Ti awon kan tun wa sa oka yooku,ti awon ti won ko kore oka gbagbe ni afonifoji Refaimu.
Ọpọlọpọ nǹkan mìíràn ni Jesu ṣe, bí a bá kọ wọ́n ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, mo rò pé kò ní sí ààyè tó ní gbogbo ayé tí yóo gba ìwé tí a bá kọ wọ́n sí.
Opolopo nnkan miiran ni Jesu se, bi a ba ko won ni okookan, mo ro pe ko ni si aaye to ni gbogbo aye ti yoo gba iwe ti a ba ko won si.
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 31 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 31 ]
Kí nìdí ?
Ki nidi ?
Lákọ̀ọ́kọ́ , wọ́n máa ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ lemọ́lemọ́ lórí tẹlifóònù láti fi mọ ara wọn dunjú .
Lakooko , won maa n ba ara won soro lemolemo lori telifoonu lati fi mo ara won dunju .
Ní ìdàkejì , tó o bá wà lára “ ogunlọ́gọ̀ ńlá ” ti “ àgùntàn mìíràn , ” Ọlọ́run ti fún ẹ ní ìrètí láti gbé lórí ilẹ̀ ayé .
Ni idakeji , to o ba wa lara " ogunlogo nla " ti " aguntan miiran , " Olorun ti fun e ni ireti lati gbe lori ile aye .
bíi wọn jẹ ẹbí to súnmọ wọn,
bii won je ebi to sunmo won,
Ọ̀gbẹ́ni yìí kọ̀wé pé : “ Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ , táwọn Kristẹni bá ń sọ̀rọ̀ nípa ‘ pẹpẹ , ’ pẹpẹ nípa tẹ̀mí ló sábà máa ń tọ́ka sí .
Ogbeni yii kowe pe : " Teletele , tawon Kristeni ba n soro nipa ' pepe , ' pepe nipa temi lo saba maa n toka si .
Ǹjẹ́ O Lè Ṣàlàyé ?
Nje O Le Salaye ?
Àpilẹ̀kọ yìí ṣàlàyé bí ẹni tó bá ní ẹ̀dùn ọkàn ṣe lè borí rẹ̀ .
Apileko yii salaye bi eni to ba ni edun okan se le bori re .
Vladimir ṣàlàyé ìdí tí ìbẹ̀rù tí kò nídìí fi mú òun , ó ní : “ Àwọn wọ̀nyí ni ẹgbẹ́ òkùnkùn táwọn aláṣẹ ní orílẹ̀ - èdè wa máa ń lò láti fi dún kùkùlajà mọ́ àwọn ọmọdé . . .
Vladimir salaye idi ti iberu ti ko nidii fi mu oun , o ni : " Awon wonyi ni egbe okunkun tawon alase ni orile - ede wa maa n lo lati fi dun kukulaja mo awon omode . . .
Ńṣe ló yẹ kí ìgbéyàwó máa fúnni láyọ̀ , kò yẹ kó máa bani nínú jẹ́ tàbí kó dà bí iṣẹ́ tí kò gbádùn mọ́ni .
Nse lo ye ki igbeyawo maa funni layo , ko ye ko maa bani ninu je tabi ko da bi ise ti ko gbadun moni .
Kí ni ohun náà ?
Ki ni ohun naa ?
ìdáǹdè
idande
ni wQn máa n jẹ ohun ìní àwọn
ni wQn maa n je ohun ini awon
Bí ọkùnrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbéyàwó, o kò gbọdọ̀ ran lọ sí ogun tàbí kí ó ní iṣẹ́ kan láti ṣe
Bi okunrin kan ba sese gbeyawo, o ko gbodo ran lo si ogun tabi ki o ni ise kan lati se
Èmi sì ti wà láàyè láìsí òfin nígbà kan rí
Emi si ti wa laaye laisi ofin nigba kan ri
“Ẹ ya ará yín sí mímọ́ láti bá a jagun!Dìde, kí a kọlù ú ní ìgbà ọ̀sán!Ṣùgbọ́n ó ṣe, nítorí ọjọ́ lọ tán,ọjọ́ alẹ́ náà sì gùn sí i.
"E ya ara yin si mimo lati ba a jagun!Dide, ki a kolu u ni igba osan!Sugbon o se, nitori ojo lo tan,ojo ale naa si gun si i.
Ètò ibùdó ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan.
Eto ibudo eya kookan.
Ábúráhámù 2018 Ṣ.S.K . , wọ́n bí ÁBÚRÁHÁMÙ
Aburahamu 2018 S.S.K . , won bi ABURAHAMU
Bí àpẹẹrẹ , bí ẹnì kan tó fẹ́ràn láti máa wà pẹ̀lú àwọn ọmọdé ju àwọn àgbà lọ bá kúndùn àti máa wà pẹ̀lú ọmọ ẹ , tó ń ra ẹ̀bùn fún un , tàbí tó sọ pé òun á máa bá ẹ bójú tó o , tó sì máa ń dá mú un jáde , kí ni wàá ṣe ?
Bi apeere , bi eni kan to feran lati maa wa pelu awon omode ju awon agba lo ba kundun ati maa wa pelu omo e , to n ra ebun fun un , tabi to so pe oun a maa ba e boju to o , to si maa n da mu un jade , ki ni waa se ?
Ìlérí Rẹ̀ ha kùnà títí ayé
Ileri Re ha kuna titi aye
má se dẹ́sẹ̀ mọ́, kí ohun tí ó burú ju èyí lọ má ba à bá ọ! Ọkùnrin náà lọ, ó sì sọ fún àwọn Júù pé, Jésù ni ẹni tí ó mú òun láradá
ma se dese mo, ki ohun ti o buru ju eyi lo ma ba a ba o! Okunrin naa lo, o si so fun awon Juu pe, Jesu ni eni ti o mu oun larada
Aláyọ̀ ni àwọn tí ń pa àwọn ìránnilétí rẹ̀ mọ́ ; wọ́n ń fi gbogbo ọkàn - àyà wá a . ” — Sáàmù 119 : 1 , 2 .
Alayo ni awon ti n pa awon irannileti re mo ; won n fi gbogbo okan - aya wa a . " -- Saamu 119 : 1 , 2 .
Ó ṣe àwọn abọ́ ńlá ati ìjókòó wọn.
O se awon abo nla ati ijokoo won.
Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé òun nìkan làwọn òbí rẹ̀ bí , ọ̀rọ̀ pé òun lè di ìyá lọ́jọ́ kan kì í fi bẹ́ẹ̀ wá sọ́kàn rẹ̀ .
Niwon bo ti je pe oun nikan lawon obi re bi , oro pe oun le di iya lojo kan ki i fi bee wa sokan re .
siwaju
siwaju
‘Èyí ẹ̀kẹfà jẹ́ oníwàrere nínú àwọn ọmọ ènìyàn ṣùgbọ́n bíi ó bá pẹ́ nínú ayé sí i ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyà ni ìbá jẹ́ ẹ́ nítorí àìsàn ńlá kan ìbá ṣe é kò bá sì tí sí oníṣègùn tí ó lè wò ó sàn bẹ́ẹ̀ ní àìsàn yìí kò bá tètè pa á, ìbá fi ìyà jẹ ẹ́ títí kí n tóó lọ mú un. Bí àìsàn yìí kòbá dé sí ọkùnrin náà ìjà ńlá kan ìbá bbẹ́ sílẹ̀ tí orílẹ̀-èdè yóó fi máa dìde sí orílẹ̀-èdè, tí ìjọba kan yóò fi máa dìde sí ìjọba kejì bẹ́ẹ̀ ni orí ọkùnrin yìí ní ìjà ìbá ti bẹ̀rẹ̀, orúkọ rẹ̀ ìbá sì bàjẹ́ láti ìrandíran. Nítorí ìwọ̀nyí ni Ọlọ́run ṣe pàṣẹ fún mi kí n lọ mú un wá síwájú Òun.
'Eyi ekefa je oniwarere ninu awon omo eniyan sugbon bii o ba pe ninu aye si i opolopo iya ni iba je e nitori aisan nla kan iba se e ko ba si ti si onisegun ti o le wo o san bee ni aisan yii ko ba tete pa a, iba fi iya je e titi ki n too lo mu un. Bi aisan yii koba de si okunrin naa ija nla kan iba bbe sile ti orile-ede yoo fi maa dide si orile-ede, ti ijoba kan yoo fi maa dide si ijoba keji bee ni ori okunrin yii ni ija iba ti bere, oruko re iba si baje lati irandiran. Nitori iwonyi ni Olorun se pase fun mi ki n lo mu un wa siwaju Oun.
Báwo la ṣe lè bọ̀wọ̀ fún àwọn tá à ń wàásù fún ?
Bawo la se le bowo fun awon ta a n waasu fun ?
“ Ní àkókò yẹn , ojú àwọn afọ́jú yóò là , etí àwọn adití pàápàá yóò sì ṣí .
" Ni akoko yen , oju awon afoju yoo la , eti awon aditi paapaa yoo si si .
Sulliman Johan Mazadou (ti a bi ni ọjọ kankanla oṣu Kẹrin ni ọdun 1985 ni Marignane, France [1] ) jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹede Niger ti o nṣere fun ẹgbẹ agbabọọlu Faranse US Marignane ni Championnat de France amateur .
Sulliman Johan Mazadou (ti a bi ni ojo kankanla osu Kerin ni odun 1985 ni Marignane, France [1] ) je agbaboolu omo orileede Niger ti o nsere fun egbe agbaboolu Faranse US Marignane ni Championnat de France amateur .
Riana sọ pé : “ Mo rí ọwọ́ Jèhófà lára mi lásìkò tí mo nílò rẹ̀ gan - an , ìyẹn sì mú kí n lè máa bá iṣẹ́ ìsìn mi lọ !
Riana so pe : " Mo ri owo Jehofa lara mi lasiko ti mo nilo re gan - an , iyen si mu ki n le maa ba ise isin mi lo !
Àwọn èèyàn máa ń ta àwọn nǹkan ìní wọn tàbí kí wọ́n jẹ gbèsè kí wọ́n lè rówó ra ẹran tí wọ́n máa fi ṣètùtù , kí wọ́n sì lè ṣayẹyẹ láti tu mọ̀lẹ́bí wọn tó ti kú lójú .
Awon eeyan maa n ta awon nnkan ini won tabi ki won je gbese ki won le rowo ra eran ti won maa fi setutu , ki won si le sayeye lati tu molebi won to ti ku loju .
Sọọlih) kí o sì ṣe sùúrú.
Soolih) ki o si se suuru.
Ohun tó kàn táá máa jíròrò nìyẹn .
Ohun to kan taa maa jiroro niyen .
Àmọ́ ṣá o , a mọ̀ pé a kò lè wà láàyè láìsí àwọn òkè ńláńlá .
Amo sa o , a mo pe a ko le wa laaye laisi awon oke nlanla .
Láti àwọn ọdún wọ̀nyí wá ni mo ti rí i pé Jèhófà máa ń tì wá lẹ́yìn tá a bá ṣáà ti lè gbẹ́kẹ̀ lé e fún okun .
Lati awon odun wonyi wa ni mo ti ri i pe Jehofa maa n ti wa leyin ta a ba saa ti le gbeke le e fun okun .
Òun fúnra rẹ̀ sọ pé : “ Èmi , Jèhófà Ọlọ́run rẹ , yóò di ọwọ́ ọ̀tún rẹ mú , Ẹni tí ń wí fún ọ pé , ‘ Má fòyà .
Oun funra re so pe : " Emi , Jehofa Olorun re , yoo di owo otun re mu , Eni ti n wi fun o pe , ' Ma foya .
Orí mi wú nígbà tí mo gbọ́ gudugudu méje àti yàyà mẹ́fà tí wọ́n ti ṣe láti jólóòótọ́ sí Ọlọ́run láìka inúnibíni sí .
Ori mi wu nigba ti mo gbo gudugudu meje ati yaya mefa ti won ti se lati joloooto si Olorun laika inunibini si .
Gbogbo wa la máa ń gbádùn àwọn ìpàdé àtàwọn àpéjọ tá a máa ń ṣe .
Gbogbo wa la maa n gbadun awon ipade atawon apejo ta a maa n se .
Bíbélì sọ pé ó yẹ kéèyàn ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀ .
Bibeli so pe o ye keeyan ni iwa irele .
Nítorí pé ńṣe ni Jèhófà dà bí olùṣọ́ àgùntàn tó wà lójúfò , tó ń ṣọ́ àwọn àgùntàn rẹ̀ lójú méjèèjì .
Nitori pe nse ni Jehofa da bi oluso aguntan to wa lojufo , to n so awon aguntan re loju mejeeji .
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni èmi àti ọkọ mi máa ń báwọn jíròrò àwọn nǹkan tẹ̀mí , a sì tún máa ń ṣeré ìdárayá pẹ̀lú wọn , kódà ọkọ mi máa ń gbá bọ́ọ̀lù pẹ̀lú wọn .
Opo igba ni emi ati oko mi maa n bawon jiroro awon nnkan temi , a si tun maa n sere idaraya pelu won , koda oko mi maa n gba boolu pelu won .
Wọ́n ti ṣe àwọn ètò tó yẹ kí wọ́n lè máa ṣe iṣẹ́ wíwàásù Ìjọba Ọlọ́run àti sísọni di ọmọ ẹ̀yìn . — Mátíù 24 : 14 ; 28 : 19 , 20 .
Won ti se awon eto to ye ki won le maa se ise wiwaasu Ijoba Olorun ati sisoni di omo eyin . — Matiu 24 : 14 ; 28 : 19 , 20 .
TÍTÚN ÀWÒRÁN TÒ
TITUN AWORAN TO
Ó wá bi Jésù pé : “ Kí ni òtítọ́ ? ”
O wa bi Jesu pe : “ Ki ni otito ? ”
èyí sì ni iye àwọn alágbára ọkùnrin Dáfídì
eyi si ni iye awon alagbara okunrin Dafidi
Yàtọ̀ síyẹn , tí ọmọ Ísírẹ́lì kan tó jẹ́ tálákà bá yá owó , Òfin kò fàyè gbà á kí wọ́n gba owó èlé lọ́wọ́ rẹ̀ .
Yato siyen , ti omo Isireli kan to je talaka ba ya owo , Ofin ko faye gba a ki won gba owo ele lowo re .
jákímù
jakimu
A óò dúró sórí òkìtì pàǹtírí tó wà níbi tí bọ́ọ̀sì máa ń dúró kó lè rọrùn fún wa láti wọlé .
A oo duro sori okiti pantiri to wa nibi ti boosi maa n duro ko le rorun fun wa lati wole .
Ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ mìíràn sì wí fún un pé, Olúwa, kọ́kọ́ jẹ́ kí èmi kí ó kọ́ lọ sìnkú bàbá mi ná
Omo-eyin re miiran si wi fun un pe, Oluwa, koko je ki emi ki o ko lo sinku baba mi na
Wọ́n sọ pé, “Nígbà tí pàṣẹ fún olúwa mi láti fi ilẹ̀ yìí fún àwọn ọmọ Israẹli gẹ́gẹ́ bí ogún nípa kèké ṣíṣẹ́. Ó pa á láṣẹ fún ọ láti fi ogún Ṣelofehadi arákùnrin wa fún àwọn ọmọbìnrin rẹ̀.
Won so pe, “Nigba ti pase fun oluwa mi lati fi ile yii fun awon omo Israeli gege bi ogun nipa keke sise. O pa a lase fun o lati fi ogun Selofehadi arakunrin wa fun awon omobinrin re.
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ̀ dáadáa pé tó bá dọ̀rọ̀ àwọn ìlànà tó yẹ káwa èèyàn máa tẹ̀ lé , Ẹlẹ́dàá mọ̀ ju ẹnikẹ́ni lọ .
Awon Elerii Jehofa mo daadaa pe to ba doro awon ilana to ye kawa eeyan maa te le , Eledaa mo ju enikeni lo .