diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Nígbà tí mo forí dáhùn pé ó wù mí , ó tún béèrè pé , “ Ṣé ó wù ẹ́ láti máa gbénú ẹ̀ ? ”
Nigba ti mo fori dahun pe o wu mi , o tun beere pe , " Se o wu e lati maa gbenu e ? "
Ojúkòkòrò tó ní mú kí ọkàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í fà sí ìyàwó oníyàwó , ó ṣàgbèrè , ó sì ṣètò pé kí wọ́n pa ọkọ obìnrin yẹn .
Ojukokoro to ni mu ki okan re bere si i fa si iyawo oniyawo , o sagbere , o si seto pe ki won pa oko obinrin yen .
Nítorí-èyi, èmi, Nífáì, ṣe ìwé
Nitori-eyi, emi, Nifai, se iwe
“ Èso ìmọ́lẹ̀ ní gbogbo onírúurú ohun rere àti òdodo àti òtítọ́ nínú . ” — ÉFÉSÙ 5 : 9 .
" Eso imole ni gbogbo oniruuru ohun rere ati ododo ati otito ninu . " -- EFESU 5 : 9 .
Adura Olùpọ́njú.
Adura Oluponju.
Ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí , ọ̀pọ̀ àwọn nǹkan tí ń kó ìdààmú ọkàn báni làwọn ìránṣẹ́ Jèhófà àtàwọn mìíràn ń fojú winá rẹ̀ .
Ni awon ojo ikeyin yii , opo awon nnkan ti n ko idaamu okan bani lawon iranse Jehofa atawon miiran n foju wina re .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí ọmọ tí wọ́n bí tí kò lè mọ ìwà hù , síbẹ̀ ó yẹ káwọn òbí máa fìwà rere kọ́ wọn bí wọ́n ṣe ń dàgbà .
Bo tile je pe ko si omo ti won bi ti ko le mo iwa hu , sibe o ye kawon obi maa fiwa rere ko won bi won se n dagba .
Ohun tí ẹnì kan tó sá kúrò nílé lẹ́ẹ̀mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ sọ fara jọ ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn sọ .
Ohun ti eni kan to sa kuro nile leemeta otooto so fara jo ohun ti opo eeyan so .
jàbùjàbù
jabujabu
Ó kẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ lọ́dún 1957 , ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe aṣáájú - ọ̀nà lọ́dún 1958 .
O kekoo otito lodun 1957 , o si bere si i se asaaju - ona lodun 1958 .
Nígbà tí wọ́n sì ti ṣe nǹkan gbogbo tán gẹ́gẹ́ bí òfin Olúwa, wọ́n padà lọ sí Gálílì, sí Násárẹ́tì ìlú wọn
Nigba ti won si ti se nnkan gbogbo tan gege bi ofin Oluwa, won pada lo si Galili, si Nasareti ilu won
Nígbà kan tí wọ́n ń kọ́ wa lẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ní iléèwé , lemọ́lemọ́ ni àlùfáà Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì kan pa á láṣẹ fún mi pé kí ń gbé àgbélébùú kọ́rùn .
Nigba kan ti won n ko wa lekoo isin ni ileewe , lemolemo ni alufaa Otodoosi kan pa a lase fun mi pe ki n gbe agbelebuu korun .
Àkọsílẹ̀ kan tí wọ́n pè ní Mayo Clinic Health Letter sọ pé : “ Àwọn tí wọ́n sábà máa ń ṣe iṣẹ́ abẹ fún nítorí pé wọ́n sanra jọ̀kọ̀tọ̀ làwọn èèyàn tí wọ́n wà láàárín ọdún méjìdínlógún sí márùndínláàádọ́rin tí wọ́n sì wọ̀n ju ogójì BMI lọ , tí ìsanra jọ̀kọ̀tọ̀ wọn sì ń wu ìlera wọn léwu . ” — Ìkọ̀wé wínníwínní jẹ́ tiwa .
Akosile kan ti won pe ni Mayo Clinic Health Letter so pe : " Awon ti won saba maa n se ise abe fun nitori pe won sanra jokoto lawon eeyan ti won wa laaarin odun mejidinlogun si marundinlaaadorin ti won si won ju ogoji BMI lo , ti isanra jokoto won si n wu ilera won lewu . " -- Ikowe winniwinni je tiwa .
Ó sọ pé : “ Èrò mi ni pé ó ti di ẹrù iṣẹ́ tèmi náà láti máa rí i pé oko náà ń pawó wọlé . . . , àmọ́ kò ṣeé ṣe fún mi rárá . ”
O so pe : “ Ero mi ni pe o ti di eru ise temi naa lati maa ri i pe oko naa n pawo wole . . . , amo ko see se fun mi rara . ”
Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé kì í ṣe gbogbo ìjọsìn ni Ọlọ́run tẹ́wọ́ gbà .
Bibeli je ka mo pe ki i se gbogbo ijosin ni Olorun tewo gba .
Àwọn Kristẹni gbọ́dọ̀ rí i pé , ọ̀nà tí wọ́n gbà ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì kò ta ko àwọn ìlànà Bíbélì . — 1 Tímótì 1 : 5 , 19 .
Awon Kristeni gbodo ri i pe , ona ti won gba n lo Intaneeti ko ta ko awon ilana Bibeli . -- 1 Timoti 1 : 5 , 19 .
Ẹ ò ní gbàgbé ẹni tó kú náà .
E o ni gbagbe eni to ku naa .
Nígbà míì , wọ́n máa ń kó ìwé díẹ̀ wá sí pápá tó wà nítòsí ọgbà ẹ̀wọ̀n .
Nigba mii , won maa n ko iwe die wa si papa to wa nitosi ogba ewon .
Bí agbára ọ̀kan lára àwọn iṣan náà bá ṣe pọ̀ sí lè wà lára ohun tó lè mú kí ẹnì kan máa fẹ́ láti para rẹ̀ .
Bi agbara okan lara awon isan naa ba se po si le wa lara ohun to le mu ki eni kan maa fe lati para re .
Kò lè sọ̀rọ̀ rárá, nítorí tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́
Ko le soro rara, nitori ti o ni emi aimo
Torí náà , ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí wọ́n ṣe ń ra ìpín ìdókòwò àti bí wọ́n ṣe ń tà á .
Tori naa , o lo kekoo nipa bi won se n ra ipin idokowo ati bi won se n ta a .
Ó sì ṣe pé lẹ́hìn tí ọba
O si se pe lehin ti oba
Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹ̀gbọ́n Daniel obìnrin ti di akéde tí kò tíì ṣèrìbọmi .
Okan lara awon omo egbon Daniel obinrin ti di akede ti ko tii seribomi .
46 : 13 ; Náh .
46 : 13 ; Nah .
( a ) Ibo la ti lè rí àpẹẹrẹ àwọn tó lo ìkóra - ẹni - níjàánu ?
( a ) Ibo la ti le ri apeere awon to lo ikora - eni - nijaanu ?
Àmọ́ , ó lè ṣeé ṣe fún wa láti dé ọ̀dọ̀ àwọn èèyàn púpọ̀ sí i ju bá a ṣe ń ṣe nísinsìnyí lọ ní ìpínlẹ̀ ìjọ wa .
Amo , o le see se fun wa lati de odo awon eeyan pupo si i ju ba a se n se nisinsinyi lo ni ipinle ijo wa .
láàánú
laaanu
Ìròyìn tó wá láti àwọn ilẹ̀ tó wà ní apá Ìwọ̀ Oòrùn Ayé fi hàn pé ó tọ́ ká máa fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò .
Iroyin to wa lati awon ile to wa ni apa Iwo Oorun Aye fi han pe o to ka maa fi awon ilana Bibeli silo .
Bí wọ́n bá fẹ́ , wọ́n tilẹ̀ lè máa fi fọ́tò ránṣẹ́ síra wọn , kí wọ́n sì máa kọ̀wé síra wọn kí àjọṣe wọn lè lágbára .
Bi won ba fe , won tile le maa fi foto ranse sira won , ki won si maa kowe sira won ki ajose won le lagbara .
Èmi àti aláwọ̀ funfun kankan ò jọ jókòó pa pọ̀ lálàáfíà rí , ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti pé ká jọ jẹun nínú ilé wọn .
Emi ati alawo funfun kankan o jo jokoo pa po lalaafia ri , ka ma sese wa so ti pe ka jo jeun ninu ile won .
Nítorí wọ́n tọ́ wa fún ọjọ́ díẹ̀ bí o ba ti dára lójú wọn
Nitori won to wa fun ojo die bi o ba ti dara loju won
olokùn
olokun
Ìmúṣẹ Tó Pabanbarì
Imuse To Pabanbari
Èmi Olùṣe Ohun Ìjà Tẹ́lẹ̀ Wá Di Olùgba Ẹ̀mí Là
Emi Oluse Ohun Ija Tele Wa Di Olugba Emi La
Àmọ́ ṣá , Khan tí ṣàwárí pé àwọn kòkòrò tó máa ń lu ihò sára irè yìí fẹ́ràn láti máa jẹ koríko kan tó ń jẹ́ èésún .
Amo sa , Khan ti sawari pe awon kokoro to maa n lu iho sara ire yii feran lati maa je koriko kan to n je eesun .
Báwo ni ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ṣe lè fi hàn pé à ń ṣe ohun tó yẹ ẹni tó ń jẹ́ orúkọ mọ́ Ọlọ́run ?
Bawo ni eni kookan wa se le fi han pe a n se ohun to ye eni to n je oruko mo Olorun ?
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Awon Ohun To Wa Ninu Iwe Yii
Àdúrà máa ń jẹ́ ká sún mọ́ Jèhófà .
Adura maa n je ka sun mo Jehofa .
Ó dájú pé nígbà tí Mósè wà ní kékeré , Jókébédì tó jẹ́ ìyá rẹ̀ á ti kọ́ ọ ní ọ̀pọ̀ nǹkan nípa Ọlọ́run àwọn Hébérù .
O daju pe nigba ti Mose wa ni kekere , Jokebedi to je iya re a ti ko o ni opo nnkan nipa Olorun awon Heberu .
Kí ni nǹkan míì tí Aísáyà sọ tẹ́lẹ̀ nípa “ ìlú olódi ” náà ?
Ki ni nnkan mii ti Aisaya so tele nipa “ ilu olodi ” naa ?
Àwọn ẹ̀kọ́ èké wo làwọn kan gbà gbọ́ ? Báwo ni Jèhófà ṣe gbà wá lọ́wọ́ àwọn ẹ̀kọ́ èké náà ?
Awon eko eke wo lawon kan gba gbo ? Bawo ni Jehofa se gba wa lowo awon eko eke naa ?
Angẹli náà dá Manoa lóhùn pé, “Bí ẹ̀yin tilẹ̀ dá mi dúró, Èmi kì yóò jẹ ọ̀kankan nínú oúnjẹ tí ẹ̀yin yóò pèsè. Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá fẹ́ ẹ pèsè ọrẹ ẹbọ sísun, kí ẹ sì fi rú ẹbọ sí .” (Manoa kò mọ̀ pé angẹli ní i ṣe.)
Angeli naa da Manoa lohun pe, "Bi eyin tile da mi duro, Emi ki yoo je okankan ninu ounje ti eyin yoo pese. Sugbon ti eyin ba fe e pese ore ebo sisun, ki e si fi ru ebo si ." (Manoa ko mo pe angeli ni i se.)
Afọ́jú ni àwọn aṣọ́de Israẹligbogbo wọn kò mọ nǹkankan.Ajá tí ó yadi ni wọ́n,wọn kò lè gbó;oorun ni wọ́n fẹ́ràn.Wọn á dùbúlẹ̀, wọn á máa lá àlá.
Afoju ni awon asode Israeligbogbo won ko mo nnkankan.Aja ti o yadi ni won,won ko le gbo;oorun ni won feran.Won a dubule, won a maa la ala.
Ọmọ ẹ̀gbọ́n wa ọkùnrin ló ní kó lọ kọ́ bí wọ́n ṣe ń wakọ̀ , ó sì gba ìwé àṣẹ ọkọ̀ wíwà lọ́dún 1987 , nígbà tó pé ọmọ ọdún mẹ́rìndínlọ́gọ́ta [ 56 ] .
Omo egbon wa okunrin lo ni ko lo ko bi won se n wako , o si gba iwe ase oko wiwa lodun 1987 , nigba to pe omo odun merindinlogota [ 56 ] .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 10 ]
ohun kan wà tí ẹ̀kọ́ ìsìn Kristẹni jẹ́ kó yé wa , òun náà ni pé : Níwọ̀n bí Olùgbàlà ti jíǹde , ó dájú pé lọ́jọ́ kan ṣá , a ó pàdé nílé ayọ̀ . ”
ohun kan wa ti eko isin Kristeni je ko ye wa , oun naa ni pe : Niwon bi Olugbala ti jinde , o daju pe lojo kan sa , a o pade nile ayo . ”
Rárá o .
Rara o .
5 : 26 ; 6 : 53 — Kí ló túmọ̀ sí láti ní ‘ ìyè nínú ara ẹni ’ ?
5 : 26 ; 6 : 53 — Ki lo tumo si lati ni ‘ iye ninu ara eni ’ ?
Ojú wo làwọn Kristẹni tòótọ́ fi ń wo ayé , àwọn ìbéèrè wo ló sì yẹ ká bi ara wa ?
Oju wo lawon Kristeni tooto fi n wo aye , awon ibeere wo lo si ye ka bi ara wa ?
Àwọn kan sì ní ojúbọ nínú ilé wọn .
Awon kan si ni ojubo ninu ile won .
Ọlọ́run tún buyì kún wa ní ti pé ó fún wa lómìnira láti ṣe bá a ṣe fẹ́ .
Olorun tun buyi kun wa ni ti pe o fun wa lominira lati se ba a se fe .
Ṣùgbọ́n , kí lo máa ṣe tó bá jẹ́ pé bí ipò nǹkan ṣe rí fún ọ mú kó ṣòro tàbí kó tiẹ̀ jẹ́ kó ni ọ́ lára gan - an láti máa bá a lọ láti pa àwọn òfin àti ìlànà Jèhófà mọ́ ?
Sugbon , ki lo maa se to ba je pe bi ipo nnkan se ri fun o mu ko soro tabi ko tie je ko ni o lara gan - an lati maa ba a lo lati pa awon ofin ati ilana Jehofa mo ?
Nígbà tí ó tún padà dé sọ́dọ̀ wọn, Ó rí i pé wọn ń sùn, nítorí ojú wọn kún fún oorun
Nigba ti o tun pada de sodo won, O ri i pe won n sun, nitori oju won kun fun oorun
Láwọn alẹ́ ọjọ́ Monday , èmi àti màmá mi á múra Ilé Ìṣọ́ sílẹ̀ , a ó sì wá ìbéèrè fún ìpínrọ̀ kọ̀ọ̀kan , a ó wá mú ìbéèrè náà fún arákùnrin tó ń dárí Ilé Ìṣọ́ , kó lè mú èyí tó bá wù ú lára wọn .
Lawon ale ojo Monday , emi ati mama mi a mura Ile Iso sile , a o si wa ibeere fun ipinro kookan , a o wa mu ibeere naa fun arakunrin to n dari Ile Iso , ko le mu eyi to ba wu u lara won .
Láfikún sí i , mímọ̀ pé wíwo ohun arùfẹ́ - ìṣekúṣe - sókè kò dùn mọ́ Ọlọ́run nínú tún lè ràn ọ́ lọ́wọ́ síwájú sí i láti jáwọ́ nínú rẹ̀ .
Lafikun si i , mimo pe wiwo ohun arufe - isekuse - soke ko dun mo Olorun ninu tun le ran o lowo siwaju si i lati jawo ninu re .
Ó fi ìkùukùu ṣe atọ́nà wọn ní ọ̀sán,ó fi ìmọ́lẹ̀ iná tọ́ wọn sọ́nà ní gbogbo òru.
O fi ikuukuu se atona won ni osan,o fi imole ina to won sona ni gbogbo oru.
Kí Dáfídì má bàa wá àwáwí , Nátánì sọ ìtàn kan tó dájú pé ó máa wọ ọba tó ti fìgbà kan rí jẹ́ olùṣọ́ àgùntàn yìí lọ́kàn .
Ki Dafidi ma baa wa awawi , Natani so itan kan to daju pe o maa wo oba to ti figba kan ri je oluso aguntan yii lokan .
ayé òde-òní lówe lówe náa
aye ode-oni lowe lowe naa
A rọ̀ ẹ́ pé kó o ka ìdáhùn Bíbélì sí àwọn ìbéèrè yìí nínú àwọn àpilẹ̀kọ tó tẹ̀ lé e .
A ro e pe ko o ka idahun Bibeli si awon ibeere yii ninu awon apileko to te le e .
Kò lè sí omi àjàrà tí kò tíì di ọtí nígbà tí wọ́n bá ń ṣe Ìrékọjá , torí pé kò sọ́gbọ́n tí kò fi ní le sí i látìgbà tí wọ́n bá ti kórè rẹ̀ nígbà ìwọ́wé títí dìgbà tí wọ́n máa ń ṣe Ìrékọjá nígbà ìrúwé .
Ko le si omi ajara ti ko tii di oti nigba ti won ba n se Irekoja , tori pe ko sogbon ti ko fi ni le si i latigba ti won ba ti kore re nigba iwowe titi digba ti won maa n se Irekoja nigba iruwe .
Ìyẹn ò bá nǹkan tá à ń sọ mu .
Iyen o ba nnkan ta a n so mu .
Mo táràrà jáde , ọ̀dọ̀ àwọn aládùúgbò mi ni mo sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà títí tí ilẹ̀ fi mọ́ .
Mo tarara jade , odo awon aladuugbo mi ni mo si wa legbee ona titi ti ile fi mo .
iyẹ̀wu
iyewu
Iṣẹ́ ìwàásù ilé - dé - ilé ni ọ̀nà tó ṣe pàtàkì jù lọ táwọn Kristẹni ẹni àmì òróró àtàwọn alábàákẹ́gbẹ́ wọn tó jẹ́ “ àgùntàn mìíràn ” gbà ń mú àsọtẹ́lẹ̀ náà ṣẹ .
Ise iwaasu ile - de - ile ni ona to se pataki ju lo tawon Kristeni eni ami ororo atawon alabaakegbe won to je " aguntan miiran " gba n mu asotele naa se .
Ẹ̀mí àwọn wòlíì a sí máa tẹríba fún àwọn wòlíì
Emi awon wolii a si maa teriba fun awon wolii
Ẹsẹ̀ rẹ rì sínú orọ̀fọ̀
Ese re ri sinu orofo
Àbí ìrònú pé ayé ìgbà kan dáa ju ti ìsinyìí lọ ló kàn ń dà wá láàmú ni ?
Abi ironu pe aye igba kan daa ju ti isinyii lo lo kan n da wa laamu ni ?
Ẹ̀kọ́ Wo Lo Kọ́ ?
Eko Wo Lo Ko ?
Bẹ́ẹ̀ náà ló tún ṣe pàtàkì pé kí wọ́n ṣètò bí wọ́n ṣe máa pèsè ohun tọ́mọ náà nílò nípa tẹ̀mí .
Bee naa lo tun se pataki pe ki won seto bi won se maa pese ohun tomo naa nilo nipa temi .
Nígbà tí wọ́n bá mi wá síhìn-ín, n kò fi ọ̀rọ̀ náà falẹ̀. Ní ọjọ́ keji mo jókòó ní kóòtù, mo pàṣẹ kí wọ́n mú ọkunrin náà wá.
Nigba ti won ba mi wa sihin-in, n ko fi oro naa fale. Ni ojo keji mo jokoo ni kootu, mo pase ki won mu okunrin naa wa.
Bí àpẹẹrẹ , gẹ́gẹ́ bí ohun tí àkọlé kan nínú ìwé ìròyìn Manila Bulletin sọ , Báńkì Tó Ń Rí sí Ìdàgbàsókè Ilẹ̀ Éṣíà ròyìn pé “ Éṣíà lè mú ipò òṣì kúrò pátápátá láàárín ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n . ”
Bi apeere , gege bi ohun ti akole kan ninu iwe iroyin Manila Bulletin so , Banki To N Ri si Idagbasoke Ile Esia royin pe “ Esia le mu ipo osi kuro patapata laaarin odun meeedogbon . ”
Láwọn ìgbà míì , tó bá tiẹ̀ jẹ́ pé ìtẹ̀síwájú díẹ̀ ni Joel ní lọ́nà kan tàbí lọ́nà míì , a máa ń gbóríyìn fún un .
Lawon igba mii , to ba tie je pe itesiwaju die ni Joel ni lona kan tabi lona mii , a maa n gboriyin fun un .
Yóò dára kí àwa náà jèrè látinú “ ìhìn iṣẹ́ wíwúwo ” yìí nípa fífi àwọn ìlànà rẹ̀ sílò nínú ìgbésí ayé wa .
Yoo dara ki awa naa jere latinu “ ihin ise wiwuwo ” yii nipa fifi awon ilana re silo ninu igbesi aye wa .
tí wọn bá n bẹ̀rù, tí kò sí sí ònà
ti won ba n beru, ti ko si si ona
Ṣefa ni akọ̀wé gbọ̀ngàn ìdájọ́ rẹ̀. Sadoku ati Abiatari ni alufaa.
Sefa ni akowe gbongan idajo re. Sadoku ati Abiatari ni alufaa.
“ Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí , ó sì ṣàǹfààní fún kíkọ́ni , fún fífi ìbáwí tọ́ni sọ́nà , fún mímú àwọn nǹkan tọ́ . ” — 2 Tímótì 3 : 16 .
" Gbogbo Iwe Mimo ni Olorun mi si , o si sanfaani fun kikoni , fun fifi ibawi toni sona , fun mimu awon nnkan to . " -- 2 Timoti 3 : 16 .
Ìdí pàtàkì rèé tó fi yẹ ká máa gbàdúrà pé kí Ìjọba Ọlọ́run dé , kí ìfẹ́ Ọlọ́run sì ṣẹ lórí ilẹ̀ ayé .
Idi pataki ree to fi ye ka maa gbadura pe ki Ijoba Olorun de , ki ife Olorun si se lori ile aye .
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe rí i , ríra àkókò tí ó rọgbọ padà wé mọ́ “ ṣíṣàì fọwọ́ yẹpẹrẹ mú àǹfààní èyíkéyìí táa bá ní ” àti “ fífi àǹfààní kọ̀ọ̀kan ṣe ohun tó dára jù lọ . ”
Gege bi a se ri i , rira akoko ti o rogbo pada we mo " sisai fowo yepere mu anfaani eyikeyii taa ba ni " ati " fifi anfaani kookan se ohun to dara ju lo . "
Obìnrin náà wí fún un pé, mo mọ̀ pé, “Messia ń bọ̀ wá, tí a ń pè ní Kristi: Nígbà tí Òun bá dé, yóò sọ ohun gbogbo fún wa.”
Obinrin naa wi fun un pe, mo mo pe, "Messia n bo wa, ti a n pe ni Kristi: Nigba ti Oun ba de, yoo so ohun gbogbo fun wa."
síméì
simei
ti mú kí àwa wà láàyẹ̀ nígbà méjì,
ti mu ki awa wa laaye nigba meji,
Hanuni sì mú àwọn ìránṣẹ́ Dafidi ó fá apá kan irùngbọ̀n wọn, ó sì gé ààbọ̀ kúrò ní agbádá wọn, títí ó fi dé ìdí wọn, ó sì rán wọn lọ.
Hanuni si mu awon iranse Dafidi o fa apa kan irungbon won, o si ge aabo kuro ni agbada won, titi o fi de idi won, o si ran won lo.
Wọ́n ń bá ara wọn sọ̀rọ̀ gbogbo nǹkan wọ̀nyí tí ó ṣẹlẹ̀.
Won n ba ara won soro gbogbo nnkan wonyi ti o sele.
Àwọn kan nínú ìjọ ń fa ìpínyà , wọ́n sọ pé ó yẹ káwọn èèyàn máa tẹ̀ lé Òfin Mósè .
Awon kan ninu ijo n fa ipinya , won so pe o ye kawon eeyan maa te le Ofin Mose .
( a ) Kí nìdí tó fi ṣòro gan - an fáwọn kan láti kó ara wọn níjàánu nínú ọ̀ràn ìbálòpọ̀ ?
( a ) Ki nidi to fi soro gan - an fawon kan lati ko ara won nijaanu ninu oran ibalopo ?
Bí àpẹẹrẹ , èdè kan náà ni gbogbo èèyàn ń sọ nígbà yẹn .
Bi apeere , ede kan naa ni gbogbo eeyan n so nigba yen .
Kí nìdí tí ìwé táwọn èèyàn ò kóyán rẹ̀ kéré rárá lórí ìtàn Ṣọ́ọ̀ṣì Roman Kátólíìkì fi sọ irú ọ̀rọ̀ tó burú jáì báyẹn nípa póòpù kan àti ìdílé rẹ̀ ?
Ki nidi ti iwe tawon eeyan o koyan re kere rara lori itan Soosi Roman Katoliiki fi so iru oro to buru jai bayen nipa poopu kan ati idile re ?
Ìròyìn náà sọ pé , formaldehyde máa ń tú sínú afẹ́fẹ́ láti ara àwọn nǹkan ìkọ́lé bí i pátákó tí wọ́n tẹ́ sílẹ̀ àtàwọn ìjókòó .
Iroyin naa so pe , formaldehyde maa n tu sinu afefe lati ara awon nnkan ikole bi i patako ti won te sile atawon ijokoo .
Káyọ̀dé : Èmi náà sọ bẹ́ẹ̀ , àmọ́ ó yà mí lẹ́nu gan - an nígbà tí ẹni tá a jọ ń ṣiṣẹ́ sọ pé ẹ ò gba Jésù gbọ́ .
Kayode : Emi naa so bee , amo o ya mi lenu gan - an nigba ti eni ta a jo n sise so pe e o gba Jesu gbo .
Àwòrán táwọn ayàwòrán ń yà lákòókò yẹn fi hàn pé ìgbàgbọ́ wọn nìyẹn .
Aworan tawon ayaworan n ya lakooko yen fi han pe igbagbo won niyen .
Bí àwọn ọmọ rẹ bá ní ìwà ọmọlúwàbí tí wọ́n sì mọ ọpẹ́ dá , wọ́n á lè ní àjọṣe tó wà pẹ́ títí tó sì ṣe tímọ́tímọ́ pẹ̀lú àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe ń dàgbà .
Bi awon omo re ba ni iwa omoluwabi ti won si mo ope da , won a le ni ajose to wa pe titi to si se timotimo pelu awon eeyan bi won se n dagba .
Kò sí iyè méjì pé bọ́jọ́ ti ń gorí ọjọ́ , ẹ tún máa ronú kan àkòrí míì tẹ́ ẹ lè jíròrò .
Ko si iye meji pe bojo ti n gori ojo , e tun maa ronu kan akori mii te e le jiroro .
Bí àpẹẹrẹ , òǹkọ̀wé kan sọ pé ẹ̀sìn Ìsìláàmù “ mú ọ̀làjú ńláńlá . . . [ tó ti ] ṣe gbogbo ayé làǹfààní wá . ”
Bi apeere , onkowe kan so pe esin Isilaamu “ mu olaju nlanla . . . [ to ti ] se gbogbo aye lanfaani wa . ”
Ọkùnrin kan tó ń jẹ́ George tó ń gbé ní orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà ti ṣègbéyàwó lọ́dún mọ́kàndínlọ́gọ́ta sẹ́yìn .
Okunrin kan to n je George to n gbe ni orile - ede Amerika ti segbeyawo lodun mokandinlogota seyin .
Nínú àwọn ọ̀ràn bíi mélòó kan , wọ́n fìdí àwọn ìpinnu tí Ìgbìmọ̀ Tó Túmọ̀ Bíbélì Ayé Tuntun ṣe múlẹ̀ pé kí wọ́n dá orúkọ Jèhófà padà sí àwọn ibi tí wọ́n ti yọ ọ́ kúrò nínú ẹ̀dà ti àwọn Masorete .
Ninu awon oran bii meloo kan , won fidi awon ipinnu ti Igbimo To Tumo Bibeli Aye Tuntun se mule pe ki won da oruko Jehofa pada si awon ibi ti won ti yo o kuro ninu eda ti awon Masorete .
ṣáfátì
safati
Àwọn ìwé Bíbélì àfọwọ́kọ ìgbàanì ni wọ́n gbé ọ̀pọ̀ àwọn ìtumọ̀ Bíbélì òde òní tó ṣeé gbára lé kà .
Awon iwe Bibeli afowoko igbaani ni won gbe opo awon itumo Bibeli ode oni to see gbara le ka .
ọké
oke
Báwo la ṣe lè wá fi owó sí àyè rẹ̀ ?
Bawo la se le wa fi owo si aye re ?
Òtítọ́ wọ̀nyí nípa ìwà rere kì í ṣe èyí tí àwọn ẹ̀dá aláìpé hùmọ̀ ; ìlànà tí Ọlọ́run mí sí ni , kò sì yí wọn padà rí .
Otito wonyi nipa iwa rere ki i se eyi ti awon eda alaipe humo ; ilana ti Olorun mi si ni , ko si yi won pada ri .