diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Ẹ̀jẹ̀ tí Jésù fi rúbọ ló fìdí májẹ̀mú tuntun múlẹ̀ . | Eje ti Jesu fi rubo lo fidi majemu tuntun mule . |
Bíi ti Jóòbù , ó lè gba pé kí àwa náà sapá gidigidi ká tó lè rí àwọn ohun tí Ọlọ́run ń ṣe fún wa . | Bii ti Joobu , o le gba pe ki awa naa sapa gidigidi ka to le ri awon ohun ti Olorun n se fun wa . |
Inú ìwé Dáníẹ́lì 7 : 13 , 14 ló wà . | Inu iwe Danieli 7 : 13 , 14 lo wa . |
Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀:Ìgbókùnró kò fìdímúlẹ̀,wọn kò taṣọ agbọ́kọ̀rìn,lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkógun ni a ó pínàní arọ pẹ̀lú yóò ru ìkógun lọ. | Gbogbo okun re ni o ti de:Igbokunro ko fidimule,won ko taso agbokorin,leyin naa, opolopo ikogun ni a o pinani aro pelu yoo ru ikogun lo. |
Àrùn ojú pípọ́n tí ń ṣepin lè fa ìfọ́jú nípa dídá àpá sí ẹyinjú . | Arun oju pipon ti n sepin le fa ifoju nipa dida apa si eyinju . |
Àwọn Ìṣòro Àti Àwọn Ìdẹwò | Awon Isoro Ati Awon Idewo |
Mo fẹ́ràn wọn gan - an , ohun tí mo sì fẹ́ ni pé káwọn náà kọ́ nípa Jèhófà kí wọ́n bàa lè láyọ̀ pẹ̀lú . | Mo feran won gan - an , ohun ti mo si fe ni pe kawon naa ko nipa Jehofa ki won baa le layo pelu . |
Ní ilé ẹjọ́ àwọn Júù , irú ojú tí wọ́n fi ń wo ẹ̀rí àwọn ẹrú ni wọ́n fi ń wo ẹ̀rí tí obìnrin bá jẹ́ . | Ni ile ejo awon Juu , iru oju ti won fi n wo eri awon eru ni won fi n wo eri ti obinrin ba je . |
gbígbẹ̀ | gbigbe |
Ìfẹ́ agbára ki jẹ ki wọn fẹ gbe ipò silẹ̀ nítorí eyi wọn á fi ẹ̀sìn da ilú rú | Ife agbara ki je ki won fe gbe ipo sile nitori eyi won a fi esin da ilu ru |
Nítorí ẹ̀gàn àti èké tí wọn ń sọ, Pa wọn run nínú ìbínú, run wọ́n di ìgbà tí wọ́n kò ní sí mọ́ | Nitori egan ati eke ti won n so, Pa won run ninu ibinu, run won di igba ti won ko ni si mo |
Àmọ́ , ọgbọ́n Ọlọ́run ga , ó fi àyè sílẹ̀ kí àtakò tó wáyé ní ọgbà Édẹ́nì nípa bí òun ṣe ń ṣàkóso lè yanjú pátápátá . | Amo , ogbon Olorun ga , o fi aye sile ki atako to waye ni ogba Edeni nipa bi oun se n sakoso le yanju patapata . |
Àmọ́ , ó yẹ ká fi sọ́kàn pé “ gbogbo wa ni a máa ń kọsẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà ” nínú ọ̀rọ̀ sísọ . | Amo , o ye ka fi sokan pe “ gbogbo wa ni a maa n kose lopo igba ” ninu oro siso . |
ìjẹ̀rìí | ijerii |
Ohùn kan náà ni, nítorí náà ni èmi ṣe sọ:‘Òun a pa ẹni òtítọ́ àti ènìyàn búburú pẹ̀lú.’ | Ohun kan naa ni, nitori naa ni emi se so:'Oun a pa eni otito ati eniyan buburu pelu.' |
Ọjọ́ ìrántí ni ọjọ́ yìí yóo jẹ́ fún yín, ní ọdọọdún ni ẹ óo sì máa ṣe àjọ̀dún rẹ̀ fún OLUWA; àwọn arọmọdọmọ yín yóo sì máa ṣe àjọ̀dún yìí bí ìlànà, gẹ́gẹ́ bí ohun ìrántí títí lae. | Ojo iranti ni ojo yii yoo je fun yin, ni odoodun ni e oo si maa se ajodun re fun OLUWA; awon aromodomo yin yoo si maa se ajodun yii bi ilana, gege bi ohun iranti titi lae. |
60. Ṣé ẹ̀yin ni ẹ dá a ni àbí Àwa? | 60. Se eyin ni e da a ni abi Awa? |
( Ka Hébérù 11 : 24 - 27 . ) | ( Ka Heberu 11 : 24 - 27 . ) |
Òun kì yóò kọ̀ ọ́ tì tàbí kí ó fi ọ́ sílẹ̀ títí gbogbo iṣẹ́ tí ó jẹ́ ti iṣẹ́ ìsìn ilé Jèhófà yóò fi parí . ” | Oun ki yoo ko o ti tabi ki o fi o sile titi gbogbo ise ti o je ti ise isin ile Jehofa yoo fi pari . " |
Àwọn idì ńlá méjì yẹn dúró fún àwọn alákòóso Bábílónì àti Íjíbítì . | Awon idi nla meji yen duro fun awon alakooso Babiloni ati Ijibiti . |
Kí Olúwa sì ya ilẹ̀ yí sí mímọ́ | Ki Oluwa si ya ile yi si mimo |
Ṣò ó ń ṣàníyàn lórí ipa tí tẹlifíṣọ̀n lè máa ní lórí ìdílé rẹ ? | So o n saniyan lori ipa ti telifison le maa ni lori idile re ? |
O ti mú ìlérí tí o ṣe fún iranṣẹ rẹ, Dafidi, baba mi, ṣẹ. O ṣe ìlérí fún un nítòótọ́, o sì mú un ṣẹ lónìí. | O ti mu ileri ti o se fun iranse re, Dafidi, baba mi, se. O se ileri fun un nitooto, o si mu un se lonii. |
ìfẹ̀ṣẹ̀ | ifese |
Angẹli tí ń bá mi sọ̀rọ̀ sì jáde lọ, ó sì wí fún mi pé, “Gbé ojú rẹ sókè nísinsin yìí, kí o sì wo nǹkan tí yóò jáde lọ.” | Angeli ti n ba mi soro si jade lo, o si wi fun mi pe, “Gbe oju re soke nisinsin yii, ki o si wo nnkan ti yoo jade lo.” |
Wo ohun tí ọkùnrin tó ní ìgbẹ́kẹ̀lé kíkún nínú Ọlọ́run sọ ! | Wo ohun ti okunrin to ni igbekele kikun ninu Olorun so ! |
Jèhófà ni Bíbélì pe orúkọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo tó wà . | Jehofa ni Bibeli pe oruko Olorun tooto kan soso to wa . |
Mọ Ọlọrun ní gbogbo ọ̀nà rẹ,yóo sì mú kí ọ̀nà rẹ tọ́. | Mo Olorun ni gbogbo ona re,yoo si mu ki ona re to. |
Ọkunrin náà bá mú mi pada wá sí ẹnu ọ̀nà Tẹmpili, mo sì rí i tí omi kan ń sun láti abẹ́ ìlẹ̀kùn àbájáde ó ń ṣàn lọ sí ìhà ìlà oòrùn, ìhà ìlà oòrùn ni tẹmpili kọjú sí. Omi náà ń ṣàn láti apá gúsù ibi ìlẹ̀kùn àbájáde tí ó wà ni ìhà gúsù pẹpẹ ìrúbọ. | Okunrin naa ba mu mi pada wa si enu ona Tempili, mo si ri i ti omi kan n sun lati abe ilekun abajade o n san lo si iha ila oorun, iha ila oorun ni tempili koju si. Omi naa n san lati apa gusu ibi ilekun abajade ti o wa ni iha gusu pepe irubo. |
John tá a mẹ́nu kàn nínú àpilẹ̀kọ àkọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ sí í kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì bákan náà . | John ta a menu kan ninu apileko akoko bere si i kekoo Bibeli bakan naa . |
Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà,ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an. | Oko tabi ida, tabi ofa,eni ti o sa a ko le ran an. |
Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ Ọba Aláṣẹ Ayé òun Ọ̀run , kò jẹ́ gba ọrẹ tó lábùkù bẹ́ẹ̀ ! | Ka ma sese wa so Oba Alase Aye oun Orun , ko je gba ore to labuku bee ! |
Ẹ wo bí èyí ti fi wá lọ́kàn balẹ̀ tó pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa ! | E wo bi eyi ti fi wa lokan bale to pe Jehofa nifee wa ! |
Ìwọ̀nyí ni ààlà àyíká ènìyàn Júdà ní agbo ilé wọn | Iwonyi ni aala ayika eniyan Juda ni agbo ile won |
gbogbo agbègbè náà ni yóò jẹ́ mímọ́ | gbogbo agbegbe naa ni yoo je mimo |
Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún dírágónì náà, nítorí tí o fún ẹranko náà ní àṣẹ, wọn sì foríbalẹ̀ fún ẹranko náà, wí pé, Ta ni o dàbí ẹranko yìí | Won si foribale fun diragoni naa, nitori ti o fun eranko naa ni ase, won si foribale fun eranko naa, wi pe, Ta ni o dabi eranko yii |
Olúwa rán mi lọ sí Bétélì | Oluwa ran mi lo si Beteli |
Tító ló tóbi bàńku oi | Tito lo tobi banku oi |
Àmọ́ ṣá o , bíbẹ̀rẹ̀ sí dọ́rẹ̀ẹ́ láìronú jinlẹ̀ pẹ̀lú ẹnì kan tó jẹ́ àjèjì léwu gan - an . | Amo sa o , bibere si doree laironu jinle pelu eni kan to je ajeji lewu gan - an . |
nínú wọn tí ìwọ bá ní agbára láti tàn | ninu won ti iwo ba ni agbara lati tan |
Ọdún kan péré ni wọ́n sọ pé àwọn máa fi sìn nílẹ̀ òkèèrè . | Odun kan pere ni won so pe awon maa fi sin nile okeere . |
Olúwa Ọlọ́run sì dá obìnrin láti inú egungun tí ó yọ ní ìhà ọkùnrin náà, ó sì mu obìnrin náà tọ̀ ọ́ wá | Oluwa Olorun si da obinrin lati inu egungun ti o yo ni iha okunrin naa, o si mu obinrin naa to o wa |
Apá ọ̀tún : Àwọn táa jọ ń gbé ilé míṣọ́nnárì ní Tokyo | Apa otun : Awon taa jo n gbe ile misonnari ni Tokyo |
Ẹ̀kọ́ wo la lè kọ́ nínú ìfaradà Jésù ? | Eko wo la le ko ninu ifarada Jesu ? |
Ohun tí ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí sọ ti tó láti mọ èyí tó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá lára àwọn ìwé ìgbàanì . | Ohun ti ese Iwe Mimo yii so ti to lati mo eyi to ti odo Olorun wa lara awon iwe igbaani . |
Ìyẹn yàtọ̀ sí ohun tí Jésù sọ pé kí àwọn ọmọ ẹ̀yìn òun máa ṣe . | Iyen yato si ohun ti Jesu so pe ki awon omo eyin oun maa se . |
Ní tòótọ́ , àwọn èèyàn lè gbógun ti àwọn nọ́ọ̀sì níbi iṣẹ́ ju àwọn wọ́dà tàbí àwọn ọlọ́pàá lọ , àti pé ìpín méjìléláàádọ́rin nínú ọgọ́rùn - ún àwọn nọ́ọ̀sì ni ọkàn wọn kò balẹ̀ látàrí pé wọ́n lè fipá kọ lu àwọn . ” | Ni tooto , awon eeyan le gbogun ti awon noosi nibi ise ju awon woda tabi awon olopaa lo , ati pe ipin mejilelaaadorin ninu ogorun - un awon noosi ni okan won ko bale latari pe won le fipa ko lu awon . " |
Seiss , tó jẹ́ ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn , sọ pé : “ Nígbà tí Mèsáyà bá bẹ̀rẹ̀ sí ṣàkóso , gbogbo ayé ló máa padà rí . . . bó ṣe yẹ kó rí . . . ká ní Ádámù ò dẹ́ṣẹ̀ ni . ” | Seiss , to je elekoo isin , so pe : " Nigba ti Mesaya ba bere si sakoso , gbogbo aye lo maa pada ri . . . bo se ye ko ri . . . ka ni Adamu o dese ni . " |
Ohun tí Ọbafẹ́mi ń sọ ni pé ohun èlò fún àlàyé lórí lítíréṣọ̀ ní tíọ́rì gbogbo ìmọ̀ ọgbọ́n àti òye òǹkọ̀wé kò le di mímọ́ láì lo tíọ́rì | Ohun ti Obafemi n so ni pe ohun elo fun alaye lori litireso ni tiori gbogbo imo ogbon ati oye onkowe ko le di mimo lai lo tiori |
Jèhófà tún jẹ́ káwọn ọba mìíràn tí wọ́n jẹ́ onírera kàbùkù . | Jehofa tun je kawon oba miiran ti won je onirera kabuku . |
Bí àpẹẹrẹ , wọ́n lè máa tọ́jú ara wọn , kí wọ́n máa bójú tó ibi tí wọ́n ń gbé , kí wọ́n sì máa ṣètọ́jú àwọn ẹranko tó wà nínú áàkì náà . | Bi apeere , won le maa toju ara won , ki won maa boju to ibi ti won n gbe , ki won si maa setoju awon eranko to wa ninu aaki naa . |
bíṣọ́ọ̀bù | bisoobu |
Ṣùgbọ́n olúkúlùkù yóò jókòó lábẹ́ àjàrà rẹ̀àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀,ẹnìkan kì yóò sì dẹ́rùbà wọ́n,nítorí àwọn ọmọ-ogun ti sọ̀rọ̀. | Sugbon olukuluku yoo jokoo labe ajara reati labe igi opoto re,enikan ki yoo si deruba won,nitori awon omo-ogun ti soro. |
Ó ní : “ Lóru àná , mo gbàdúrà pé kí Ọlọ́run rán ẹnì kan tó máa kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí mi , mo sì rò pé ìdáhùn àdúrà mi rèé . ” | O ni : " Loru ana , mo gbadura pe ki Olorun ran eni kan to maa ko mi lekoo Bibeli si mi , mo si ro pe idahun adura mi ree . " |
A kò sì ní fẹ́ pàdánù àǹfààní tá a ní láti máa jọ́sìn Jèhófà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú àwọn ará wa , àyàfi nítorí ìdí tí kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ . | A ko si ni fe padanu anfaani ta a ni lati maa josin Jehofa ni isokan pelu awon ara wa , ayafi nitori idi ti ko see ye sile . |
Fáráò kàgbákò ní Òkun Pupa | Farao kagbako ni Okun Pupa |
Kò pẹ́ rárá lẹ́yìn tí Ogun Àgbáyé Kejì bẹ̀rẹ̀ lóṣù September ọdún 1939 tí Ilé Ìṣọ́ November 1 fi jíròrò ìdí táwa Kristẹni kò fi ń lọ́wọ́ sí ogun àti ìṣèlú . | Ko pe rara leyin ti Ogun Agbaye Keji bere losu September odun 1939 ti Ile Iso November 1 fi jiroro idi tawa Kristeni ko fi n lowo si ogun ati iselu . |
Ó kàwé ní North Point ní Darjeeling, Índíà àti ní Gẹ̀ẹ́sì ní ìlú Windsor. | O kawe ni North Point ni Darjeeling, India ati ni Geesi ni ilu Windsor. |
6 , 7 . ( a ) Ìsapá wo ni wọ́n ṣe láti pa àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà run nígbà ìjọba Násì nílẹ̀ Jámánì , kí ló sì yọrí sí ? | 6 , 7 . ( a ) Isapa wo ni won se lati pa awon Elerii Jehofa run nigba ijoba Nasi nile Jamani , ki lo si yori si ? |
Àwọn èwe yín jẹ́ ọmọ dáadáa . | Awon ewe yin je omo daadaa . |
ẹrú tí ó jọba,òmùgọ̀ tí ó jẹun yó, | eru ti o joba,omugo ti o jeun yo, |
Wọ́n tiẹ̀ pa àwọn kan nínú wọn . | Won tie pa awon kan ninu won . |
Ẹ̀rí tó dájú wà pé ṣáájú ọdún 70 Sànmánì Kristẹni ni Mátíù àti Lúùkù ti kọ àwọn Ìwé Ìhìn Rere wọn . | Eri to daju wa pe saaju odun 70 Sanmani Kristeni ni Matiu ati Luuku ti ko awon Iwe Ihin Rere won . |
Nígbà tí obìnrin kan bímọ , ìpinnu wo ló ní láti ṣe , kí ló sì ràn án lọ́wọ́ láti ṣe ìpinnu tó tọ́ ? | Nigba ti obinrin kan bimo , ipinnu wo lo ni lati se , ki lo si ran an lowo lati se ipinnu to to ? |
Àwọn oníṣẹ́ ọnà kan máa ń lo ike , igi , tàbí ẹfun , àmọ́ òjé tí Bill ń lò fún tiẹ̀ dáa gan - an ni , nítorí ó gba ìdálẹ́kọ̀ọ́ lórí bó ṣe lè fẹ̀rọ ṣe é . | Awon onise ona kan maa n lo ike , igi , tabi efun , amo oje ti Bill n lo fun tie daa gan - an ni , nitori o gba idalekoo lori bo se le fero se e . |
ṣùgbọn ẹ̀mí yín ni Ò tàn yín jẹ | sugbon emi yin ni O tan yin je |
Ìgbà kan wà tí Bishnu tó wá láti orílẹ̀ - èdè Nepal kò mọ dòò , ó sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta . | Igba kan wa ti Bishnu to wa lati orile - ede Nepal ko mo doo , o si bi omokunrin meta . |
Ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ kan tí Éhúdù dá àti ìgboyà rẹ̀ mú kó ṣeé ṣe fún un láti pa Ẹ́gílónì ọba Móábù tó sanra jọ̀kọ̀tọ̀ . | Ogbon ewe kan ti Ehudu da ati igboya re mu ko see se fun un lati pa Egiloni oba Moabu to sanra jokoto . |
mi lọdọ olúwa rẹ̀." Ṣùgbọn | mi lodo oluwa re." Sugbon |
Waltraud sọ fún ọmọkùnrin náà pé : “ Werner , ǹjẹ́ o mọ ìdí tí mo fi wá sórílẹ̀ - èdè yín ? | Waltraud so fun omokunrin naa pe : “ Werner , nje o mo idi ti mo fi wa sorile - ede yin ? |
Àmọ́ , ó lè gba pé ká sapá gidigidi ká tó lè jẹ́ oníwà tútù . | Amo , o le gba pe ka sapa gidigidi ka to le je oniwa tutu . |
Rántí mi, Ọlọ́run mi, fún rere, nítorí fún gbogbo ohun tí mo ti ṣe fún àwọn ènìyàn yìí. | Ranti mi, Olorun mi, fun rere, nitori fun gbogbo ohun ti mo ti se fun awon eniyan yii. |
Òun ni kò jẹ́ kí èmi fúnra mi wá sọ́dọ̀ rẹ. Ṣugbọn sọ gbolohun kan, ara ọmọ-ọ̀dọ̀ mi yóo sì dá. | Oun ni ko je ki emi funra mi wa sodo re. Sugbon so gbolohun kan, ara omo-odo mi yoo si da. |
Mi ò kì í ronú mọ́ pé ìgbésí ayé mi kò jámọ́ nǹkan kan . | Mi o ki i ronu mo pe igbesi aye mi ko jamo nnkan kan . |
Ìmọ́tótó , 2 / 1 | Imototo , 2 / 1 |
Àwọn Ohun Ìrúbọ Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́. | Awon Ohun Irubo Gbodo Je Mimo. |
Látàrí èyí , gbogbo àwùjọ náà yarí , wọ́n sì sọ pé ńṣe làwọn máa sọ àwọn méjèèjì lókùúta . | Latari eyi , gbogbo awujo naa yari , won si so pe nse lawon maa so awon mejeeji lokuuta . |
Ọba Ísírẹ́lì ṣàlàyé ẹ̀mí tó wà nídìí ọ̀rọ̀ tó ń tẹnu wa jáde , ó ní : “ Ìkórìíra ní ń ru asọ̀ sókè , ṣùgbọ́n ìfẹ́ a máa bo gbogbo ìrélànàkọjá pàápàá mọ́lẹ̀ . ” | Oba Isireli salaye emi to wa nidii oro to n tenu wa jade , o ni : " Ikoriira ni n ru aso soke , sugbon ife a maa bo gbogbo irelanakoja paapaa mole . " |
Ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà bá àwọn èèyàn rẹ̀ lò lóde òní ? | Ona wo ni Jehofa gba ba awon eeyan re lo lode oni ? |
Ìyẹn jẹ́ ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún [ 1,000 ] ọdún kí wọ́n tó wá ṣe iṣẹ́ náà gangan ní ìlú Aswân lọ́dún 1902 . | Iyen je ni nnkan bi egberun [ 1,000 ] odun ki won to wa se ise naa gangan ni ilu Aswan lodun 1902 . |
Nígbà tá a bá ń gbé ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìbéèrè náà yẹ̀ wò , a máa kọ́kọ́ wo àṣìṣe tó wà nínú ìdáhùn táwọn aṣáájú ìsìn máa ń fáwọn èèyàn , lẹ́yìn náà , a óò wá wo ohun tí Bíbélì fi kọ́ni gan - an . | Nigba ta a ba n gbe okookan awon ibeere naa ye wo , a maa koko wo asise to wa ninu idahun tawon asaaju isin maa n fawon eeyan , leyin naa , a oo wa wo ohun ti Bibeli fi koni gan - an . |
Aísáyà 60 : 3 pè wọ́n ní ọba , nítorí pé wọ́n máa jẹ́ ajùmọ̀jogún pẹ̀lú Kristi nínú Ìjọba Ọlọ́run ní ọ̀run . | Aisaya 60 : 3 pe won ni oba , nitori pe won maa je ajumojogun pelu Kristi ninu Ijoba Olorun ni orun . |
Ṣugbọn Jakọbu lọ sí Sukotu o kọ́ ilé kan fún ara rẹ̀ ó sì ṣe àtíbàbà fún àwọn ẹran rẹ̀. Nítorí náà ni wọ́n Ṣe ń pe ibẹ̀ ní Sukotu. | Sugbon Jakobu lo si Sukotu o ko ile kan fun ara re o si se atibaba fun awon eran re. Nitori naa ni won Se n pe ibe ni Sukotu. |
Ó mú kí irin àáké léfòó . — 2 Àwọn Ọba 6 : 5 - 7 . | O mu ki irin aake lefoo . — 2 Awon Oba 6 : 5 - 7 . |
75. Àti àwọn tò fì gbàdúrà pé | 75. Ati awon to fi gbadura pe |
Àwọn olórí kan ara Asia, tí i ṣe ọ̀rẹ́ rẹ̀, ránṣẹ́ sí i, wọ́n bẹ̀ ẹ́ pé, kí ó má ṣe fi ara rẹ̀ wéwu nínú ilé ìṣeré náà. | Awon olori kan ara Asia, ti i se ore re, ranse si i, won be e pe, ki o ma se fi ara re wewu ninu ile isere naa. |
Wọ́n tún rí àwọn ìsọfúnni nípa iye ọdún tó lò lọ́gbà ẹ̀wọ̀n . | Won tun ri awon isofunni nipa iye odun to lo logba ewon . |
Nítorí mo fi iye ọdún tí wọ́n fi ṣẹ̀ fún ọ gẹ́gẹ́ bí iye ọjọ́ tí ìwọ yóò lò. Nítorí náà, ìwọ yóò ru ẹ̀ṣẹ̀ ilé Israẹli fún irínwó ọjọ́ ó dín mẹ́wàá (390). | Nitori mo fi iye odun ti won fi se fun o gege bi iye ojo ti iwo yoo lo. Nitori naa, iwo yoo ru ese ile Israeli fun irinwo ojo o din mewaa (390). |
Bákan náà , gbígbin Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sínú ọkàn wa á ràn wá lọ́wọ́ láti yàgò fún sísọ àwọn ọ̀rọ̀ tó lè dun àwọn ẹlòmíràn . | Bakan naa , gbigbin Oro Olorun sinu okan wa a ran wa lowo lati yago fun siso awon oro to le dun awon elomiran . |
Ohun tí wọ́n rí yìí ló mú kí ọ̀jọ̀gbọ́n kan nípa òṣèlú ní Yunifásítì Brasília sọ pé : “ Gbogbo ọ̀wọ́ àwọn èèyàn tó wà ní Brazil pátá lohun tó ṣẹlẹ̀ yìí nàka àbùkù sí . ” | Ohun ti won ri yii lo mu ki ojogbon kan nipa oselu ni Yunifasiti Brasilia so pe : “ Gbogbo owo awon eeyan to wa ni Brazil pata lohun to sele yii naka abuku si . ” |
Dé ìwọ̀n àyè kan , bọ́rọ̀ ṣe rí nìyẹn fún gbogbo Kristẹni tó jẹ́ olóòótọ́ . | De iwon aye kan , boro se ri niyen fun gbogbo Kristeni to je oloooto . |
Karnaini o lẹ̀ jẹ wọn níyà, o sì lẹ | Karnaini o le je won niya, o si le |
Ìwọ̀n: | Iwon: |
Ọ̀wọ́n gógó oúnjẹ lè wà . | Owon gogo ounje le wa . |
rááráá | raaraa |
Àmọ́ ṣá o , bó tilẹ̀ jẹ́ pé a gbé ẹrù iṣẹ́ “ títọ́ [ àwọn ọmọ ] dàgbà nínú ìbáwí àti ìlànà èrò orí Jèhófà ” lé àwọn òbí lọ́wọ́ , kò sẹ́ni tó lè fọwọ́ sọ̀yà pé yóò kẹ́sẹ járí . | Amo sa o , bo tile je pe a gbe eru ise “ tito [ awon omo ] dagba ninu ibawi ati ilana ero ori Jehofa ” le awon obi lowo , ko seni to le fowo soya pe yoo kese jari . |
ìbọ̀rìṣà, oṣó, odì-yíyàn, ìjà, owú-jíjẹ, ìrúnú, ọ̀kánjúwà, ìyapa, rìkíṣí; | iborisa, oso, odi-yiyan, ija, owu-jije, irunu, okanjuwa, iyapa, rikisi; |
Àwọn ohun ìnàjú tí kò dára wà káàkiri , kódà wọ́n ń yọ́ kẹ́lẹ́ wọnú ilé ẹni nípasẹ̀ ìwé , tẹlifíṣọ̀n , Íńtánẹ́ẹ̀tì , àti fídíò . | Awon ohun inaju ti ko dara wa kaakiri , koda won n yo kele wonu ile eni nipase iwe , telifison , Intaneeti , ati fidio . |
Àwọn ọ̀dọ́ tá a jọ ń ṣe ẹgbẹ́ ní ṣọ́ọ̀ṣì wá wò mí bí ìgbà mélòó kan , àmọ́ nígbà tó yá wọn ò wá mọ́ . | Awon odo ta a jo n se egbe ni soosi wa wo mi bi igba meloo kan , amo nigba to ya won o wa mo . |
Má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ dàrútàbí kí o bẹ̀rù nígbà tía bá gbọ́ àhesọ ọ̀rọ̀ ní ilẹ̀ wa;àhesọ ọ̀rọ̀ kan wá ní ọdún yìí,òmíràn ní ọdún mìíràn àhesọ ọ̀rọ̀ ni ti ìwà ipání ilẹ̀ náà àti tí aláṣẹ kan sí aláṣẹ kejì. | Ma se je ki okan re darutabi ki o beru nigba tia ba gbo aheso oro ni ile wa;aheso oro kan wa ni odun yii,omiran ni odun miiran aheso oro ni ti iwa ipani ile naa ati ti alase kan si alase keji. |