diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
O sì lè ṣèwádìí lórí kókó yẹn tó o bá ní ìwé Watch Tower Publications Index tàbí Watchtower Library ( CD - ROM ) [ Àkójọ Ìwé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tá A Ṣe Sínú Àwo Pẹlẹbẹ Tá À Ń Fi Kọ̀ǹpútà Lò ] .
O si le sewadii lori koko yen to o ba ni iwe Watch Tower Publications Index tabi Watchtower Library ( CD - ROM ) [ Akojo Iwe Awa Elerii Jehofa Ta A Se Sinu Awo Pelebe Ta A N Fi Konputa Lo ] .
Nítorí tí a ti fún yin ni àǹfààní, kì í ṣe láti gba Kristi gbọ́ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí rẹ̀ pẹ̀lú:
Nitori ti a ti fun yin ni anfaani, ki i se lati gba Kristi gbo nikan, sugbon lati jiya nitori re pelu:
Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Awon Ohun To Wa Ninu Iwe Yii
Èyí ni ohun tí wíẸni náà tí ó la ọ̀nà nínú Òkun,ipa ọ̀nà láàrín alagbalúgbú omi,
Eyi ni ohun ti wiEni naa ti o la ona ninu Okun,ipa ona laarin alagbalugbu omi,
Ní ọjọ́ kinni oṣù keji, ní ọdún keji tí àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, OLUWA sọ fún Mose ninu Àgọ́ Àjọ, tí ó wà ninu aṣálẹ̀ Sinai, pé,
Ni ojo kinni osu keji, ni odun keji ti awon omo Israeli jade kuro ni ile Ijipti, OLUWA so fun Mose ninu Ago Ajo, ti o wa ninu asale Sinai, pe,
Bákan náà , Bíbélì sọ pé ọkùnrin ará Etiópíà náà jẹ́ akápò ọba tó “ lọ jọ́sìn ní Jerúsálẹ́mù . ” — Ìṣe 8 : 27 .
Bakan naa , Bibeli so pe okunrin ara Etiopia naa je akapo oba to " lo josin ni Jerusalemu . " -- Ise 8 : 27 .
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń bá ìgbòkègbodò wọn gẹ́gẹ́ bíi Kristẹni bọ̀ láti ọdún 1975 ní Armenia .
Awon Elerii Jehofa ti n ba igbokegbodo won gege bii Kristeni bo lati odun 1975 ni Armenia .
Ṣùgbọ́n ọjọ́ keje ni ọjọ́ ìsinmi Ọlọ́run rẹ: nínú rẹ̀ ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́kíṣẹ́ kan: ìwọ, àti ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin, ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ ọkùnrin àti ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ obìnrin, àti akọ màlúù rẹ, àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ, àti ohun ọ̀sìn rẹ kan, àti àlejò tí ń bẹ nínú ibodè rẹ; kí ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ ọkùnrin àti ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ obìnrin kí ó lè sinmi gẹ́gẹ́ bí ìwọ.
Sugbon ojo keje ni ojo isinmi Olorun re: ninu re iwo ko gbodo se isekise kan: iwo, ati omo re okunrin ati omo re obinrin, omo odo re okunrin ati omo odo re obinrin, ati ako maluu re, ati ketekete re, ati ohun osin re kan, ati alejo ti n be ninu ibode re; ki omo odo re okunrin ati omo odo re obinrin ki o le sinmi gege bi iwo.
Ẹ ò rí i pé ó ṣe pàtàkì púpọ̀ pé ká sapá ká lè rí ojú rere Jèhófà !
E o ri i pe o se pataki pupo pe ka sapa ka le ri oju rere Jehofa !
Tá a bá ń gbọ́rọ̀ sí i lẹ́nu , a óò rí ìyè àìnípẹ̀kun . — Ìṣe 3 : 23 .
Ta a ba n gboro si i lenu , a oo ri iye ainipekun . -- Ise 3 : 23 .
Àwọn ibì kan sì tún wà tó jẹ́ pé ibi tí ilé ẹ̀kọ́ wà ti jìnnà jù tàbí kó tiẹ̀ máà sí rárá .
Awon ibi kan si tun wa to je pe ibi ti ile eko wa ti jinna ju tabi ko tie maa si rara .
Ó fẹ́rẹ̀ dàbí pé ìmọ̀ nípa ẹ̀sìn àti ìfojúẹ̀sìnwoèdè ni a lè sọ pé ó gbìyànjú díẹ̀ láti gbé èrò nípa orírun èdè yọ Olówóòkéré ṣe àgbékalẹ̀ ohun tí ó kà nípa orirun èdè nínú ìwé Maya tí a ń pè ní pé lẹ́yìn tí Ẹlẹ́dàá dá ohun gbogbo nǹkan tán ló dá àwa ènìyàn láti sọ̀rọ̀ Ó sì fún àwọn ènìyàn ní agbára láti fún èdè yòókù ní orúkọ Wọ́n gbà nínú ìtàn iwase wọ́n pé àwọn ẹranko náà ní ọ̀nà tí wọ́n ń gbà fi èrò inú wọn hàn ṣùgbọ́n akitiyan láti ní èdè wọn já sí òtubáńtẹ́ Ó ṣe é ṣe kó jẹ́ pé olú ìmísí àbí ìwádìí tí àwọn onímọ̀ ẹ̀dáèdè ṣe nìyí tí wọ́n fi sọ pé èdè jẹ́ ohun àdámọ́ ÀBÙDÁ ÈDÈ
O fere dabi pe imo nipa esin ati ifojuesinwoede ni a le so pe o gbiyanju die lati gbe ero nipa orirun ede yo Olowookere se agbekale ohun ti o ka nipa orirun ede ninu iwe Maya ti a n pe ni pe leyin ti Eledaa da ohun gbogbo nnkan tan lo da awa eniyan lati soro O si fun awon eniyan ni agbara lati fun ede yooku ni oruko Won gba ninu itan iwase won pe awon eranko naa ni ona ti won n gba fi ero inu won han sugbon akitiyan lati ni ede won ja si otubante O se e se ko je pe olu imisi abi iwadii ti awon onimo edaede se niyi ti won fi so pe ede je ohun adamo ABUDA EDE
Nítorí ọkùnrin náà lára ẹni tí a ṣe iṣẹ́ ààmì ìmúláradá, ju ẹni ogójì ọdún lọ.
Nitori okunrin naa lara eni ti a se ise aami imularada, ju eni ogoji odun lo.
BÍ A bá sọ pé , bẹ́ẹ̀ ni , ìbéèrè míì ni pé : Ǹjẹ́ ìwà wa lè múnú Ọlọ́run dùn tàbí kó bà á nínú jẹ́ ?
BI A ba so pe , bee ni , ibeere mii ni pe : Nje iwa wa le munu Olorun dun tabi ko ba a ninu je ?
Ó ṣàlàyé pé : “ Mo ti wá rí i pé ọ̀nà tó dára jù lọ láti borí wọn ni pé kí n tètè sọ fún Jèhófà Ọlọ́run nípa wọn .
O salaye pe : “ Mo ti wa ri i pe ona to dara ju lo lati bori won ni pe ki n tete so fun Jehofa Olorun nipa won .
Jésù tẹ̀ lé àpẹẹrẹ bàbá ẹ̀ , ó lágbára ó sì tún jẹ́ èèyàn pẹ̀lẹ́ .
Jesu te le apeere baba e , o lagbara o si tun je eeyan pele .
Ẹ ò rí i pé ọ̀rọ̀ yìí tuni nínú gan - an !
E o ri i pe oro yii tuni ninu gan - an !
Torí pé a jẹ́ ọmọ ẹ̀yìn Jésù , à ń sọ ète Jèhófà nípa ọjọ́ iwájú fáwọn èèyàn ( Wo ìpínrọ̀ 5 àti 6 )
Tori pe a je omo eyin Jesu , a n so ete Jehofa nipa ojo iwaju fawon eeyan ( Wo ipinro 5 ati 6 )
WÁ ÌDÁHÙN SÍ ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ :
WA IDAHUN SI AWON IBEERE YII :
Gbogbo ẹni tí kò bá jẹ́wọ́ bẹ́ẹ̀ kì í ṣe ti Ọlọrun. Alátakò Kristi tí ẹ ti gbọ́ pé ó ń bọ̀ ni irú ẹni bẹ́ẹ̀. Ó ti dé inú ayé nisinsinyii.
Gbogbo eni ti ko ba jewo bee ki i se ti Olorun. Alatako Kristi ti e ti gbo pe o n bo ni iru eni bee. O ti de inu aye nisinsinyii.
Nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé òmìnira ni mo wà, tí n kò sì sí lábẹ́ ẹnìkan, sibẹ mo sọ ara mi di ẹrú gbogbo eniyan kí n lè mú ọpọlọpọ wọn wá sọ́dọ̀ Jesu.
Nitori bi o tile je pe ominira ni mo wa, ti n ko si si labe enikan, sibe mo so ara mi di eru gbogbo eniyan ki n le mu opolopo won wa sodo Jesu.
Irú èrò tí Sátánì máa fẹ́ ká ní nìyẹn .
Iru ero ti Satani maa fe ka ni niyen .
Òjò ọ̀gànjọ́ ò pa ẹni rere; bí kò pa jalè-jalè a pa yíde-yíde.
Ojo oganjo o pa eni rere; bi ko pa jale-jale a pa yide-yide.
Kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò, bí èélá náà bá ràn ká awọ ara rẹ̀, kí àlùfáà fihàn pé kò mọ́. Ààrùn ara tí ń ràn ni èyí.
Ki alufaa ye e wo, bi eela naa ba ran ka awo ara re, ki alufaa fihan pe ko mo. Aarun ara ti n ran ni eyi.
Ǹjẹ́ inú wa ò dùn pé Ọlọ́run wa kò ní fi wá sílẹ̀ ?
Nje inu wa o dun pe Olorun wa ko ni fi wa sile ?
Nípa títẹ̀ lé ìmọ̀ràn Pétérù , báwo làwọn aya tó jẹ́ Kristẹni ṣe lè ran ọkọ wọn aláìgbàgbọ́ lọ́wọ́ ?
Nipa tite le imoran Peteru , bawo lawon aya to je Kristeni se le ran oko won alaigbagbo lowo ?
Ọ̀dọ́kùnrin kan tó jẹ́ Kristẹni sọ pé : “ Nígbà tí mo wà lọ́mọ ọdún méjìlá , bàbá mi já ìdílé wa sílẹ̀ .
Odokunrin kan to je Kristeni so pe : " Nigba ti mo wa lomo odun mejila , baba mi ja idile wa sile .
Allah ni ohun gbogbo tí n bẹ ni
Allah ni ohun gbogbo ti n be ni
Dájúdájú , nígbà náà , Ọlọ́run kì yóò ha mú kí a ṣe ìdájọ́ òdodo fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ tí ń ké jáde sí i tọ̀sán - tòru , kódà bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ní ìpamọ́ra sí wọn ?
Dajudaju , nigba naa , Olorun ki yoo ha mu ki a se idajo ododo fun awon ayanfe re ti n ke jade si i tosan - toru , koda bi o tile je pe o ni ipamora si won ?
Ohun tí wọ́n máa ń ṣe níbẹ̀ ni pé wọ́n á máa sáré wọ́n á sì máa fo ohunkóhun tó bá wà lọ́nà ì báà jẹ́ ilé , ògiri tàbí àtẹ̀gùn , bẹ́ẹ̀ sì rèé wọn kì í lo ohunkóhun tó lè dáàbò bò wọ́n .
Ohun ti won maa n se nibe ni pe won a maa sare won a si maa fo ohunkohun to ba wa lona i baa je ile , ogiri tabi ategun , bee si ree won ki i lo ohunkohun to le daabo bo won .
Ó tó oṣù díẹ̀ lẹ́yìn náà káwọn amòye náà tó lọ . ”
O to osu die leyin naa kawon amoye naa to lo . ”
Kí a tó dìbò yìí, a ti yàn mí gẹ́gẹ́ bí igbá-kejì ààrẹ ìgbìmọ̀ akẹ́kọ̀ọ́ fún oṣù mẹ́jọ gbáko, kò sì sí ohun kan tí ó ṣẹlẹ̀. Ní ìdakèjì, lẹ́yìn gbogbo ìṣẹ̀lẹ̀ẹ pàjáwìrì wọ̀nyìí, kò sí àní-àní pé àjọ kan ń gbìyànjú láti tìka bọ ìṣẹ̀lẹ̀ wọ̀nwọ̀nyí ní bírípó. Ó pani lẹ́rìn-ín pé láti ìgbà yìí wá tí mo ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí igbá-kejì ààrẹ, bí mo ti ṣe ń ṣe ètò oríṣiríṣi tí n ò sì yé fi àwọn àṣàyàn ìhùwàsí mi l'éde, ṣùgbọ́n kò sí ẹni tí ó ti wádìí nípa àwọn ọ̀nà òṣèlú tí mo yàn ní ààyò.
Ki a to dibo yii, a ti yan mi gege bi igba-keji aare igbimo akekoo fun osu mejo gbako, ko si si ohun kan ti o sele. Ni idakeji, leyin gbogbo iselee pajawiri wonyii, ko si ani-ani pe ajo kan n gbiyanju lati tika bo isele wonwonyi ni biripo. O pani lerin-in pe lati igba yii wa ti mo ti n sise gege bi igba-keji aare, bi mo ti se n se eto orisirisi ti n o si ye fi awon asayan ihuwasi mi l'ede, sugbon ko si eni ti o ti wadii nipa awon ona oselu ti mo yan ni aayo.
Wọ́n bá mú ọmọ ewúrẹ́ kan ninu agbo, wọ́n pa á, wọ́n sì ti ẹ̀wù Josẹfu bọ inú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.
Won ba mu omo ewure kan ninu agbo, won pa a, won si ti ewu Josefu bo inu eje re.
Nígbà tó yá , wọ́n mọ ògiri yìí kó ga tó ẹsẹ̀ bàtà márùnlélọ́gọ́jọ [ 165 ] .
Nigba to ya , won mo ogiri yii ko ga to ese bata marunlelogojo [ 165 ] .
àti ẹ̀nìyàn, dájúdájú wọn jẹ ẹni
ati eniyan, dajudaju won je eni
Ìyàlẹ́nu gbáà ló jẹ́ fún mi lọ́jọ́ kan nígbà tí ẹni tá a jọ jẹ́ ọmọléèwé , tóun náà ní àìlera , sọ pé kí n fẹ́ òun .
Iyalenu gbaa lo je fun mi lojo kan nigba ti eni ta a jo je omoleewe , toun naa ni ailera , so pe ki n fe oun .
Nítorí kíyèsĩ, erùpẹ̀ ilẹ̀ a máa
Nitori kiyesi, erupe ile a maa
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 23 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 23 ]
Bí ẹ̀gún èṣùṣú lọ́wọ́ ọ̀mùtíni òwe lẹ́nu aláìgbọ́n.
Bi egun esusu lowo omutini owe lenu alaigbon.
síńtíkè
sintike
Ó ń ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ kan níbi tó ti jẹ́ àṣà àwọn òṣìṣẹ́ láti máa jalè .
O n sise ni ile ise kan nibi to ti je asa awon osise lati maa jale .
Kọ ohun kan tó ṣẹlẹ̀ lẹ́nu àìpẹ́ yìí , irú bí ìdánwò nílé ìwé , tó jẹ́ pé ìwọ ṣe dáadáa , àmọ́ tí ẹlòmíì ṣe dáadáa jù ẹ́ lọ .
Ko ohun kan to sele lenu aipe yii , iru bi idanwo nile iwe , to je pe iwo se daadaa , amo ti elomii se daadaa ju e lo .
A lè máà mọ gbogbo ohun tí Jósẹ́fù ń rò , ṣùgbọ́n nǹkan tó wà lọ́kàn rẹ̀ hàn kedere nínu ìdáhùn tó fún aya ọ̀gá rẹ̀ yìí , ó ní : “ Ọ̀gá mi kò mọ ohun tí ó wà pẹ̀lú mi nínú ilé , ohun gbogbo ni ó sì ti fi sí ọwọ́ mi .
A le maa mo gbogbo ohun ti Josefu n ro , sugbon nnkan to wa lokan re han kedere ninu idahun to fun aya oga re yii , o ni : " Oga mi ko mo ohun ti o wa pelu mi ninu ile , ohun gbogbo ni o si ti fi si owo mi .
Áńtíókù ( òun nìlú tí a ń pè ní Antakya , Turkey lóde òní ) wà lórí Odò Orontes tí ọkọ̀ ojú omi ń rìn kọjá , tó so ó mọ́ èbúté òkun , Seleucia Pieria , tó wà ní nǹkan bí kìlómítà mejìlélọ́gbọ̀n sí odò náà .
Antioku ( oun nilu ti a n pe ni Antakya , Turkey lode oni ) wa lori Odo Orontes ti oko oju omi n rin koja , to so o mo ebute okun , Seleucia Pieria , to wa ni nnkan bi kilomita mejilelogbon si odo naa .
Ọmọbìnrin Sioni ni a fi sílẹ̀gẹ́gẹ́ bí àtíbàbà nínú ọgbà àjàrà,gẹ́gẹ́ bí abà nínú oko ẹ̀gúnsí,àti bí ìlú tí a dó tì.
Omobinrin Sioni ni a fi silegege bi atibaba ninu ogba ajara,gege bi aba ninu oko egunsi,ati bi ilu ti a do ti.
Àwọn ìràwọ̀ , ojú ìwé 18 àti 19 : Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda United States Naval Observatory
Awon irawo , oju iwe 18 ati 19 : Nipase iyonda United States Naval Observatory
Ó ní àwọn ìkùdíẹ̀ - káàtó tirẹ̀ , bíi ti gbogbo wa .
O ni awon ikudie - kaato tire , bii ti gbogbo wa .
Lẹ́yìn táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti kọ́ Patricia lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì àtohun tó yẹ kó mọ̀ nípa ètò wọn fún ọdún mẹ́fà , ó pinnu pé òun fẹ́ máa lo àkókò púpọ̀ sí i láti wàásù , ìyẹn sì dùn mí gan - an .
Leyin tawon Elerii Jehofa ti ko Patricia lekoo Bibeli atohun to ye ko mo nipa eto won fun odun mefa , o pinnu pe oun fe maa lo akoko pupo si i lati waasu , iyen si dun mi gan - an .
Ó wá béèrè pé : “ Nítorí náà , kí ló dé tí a ò tún lè retí kí ìwà àwọn ọmọdé máa sunwọ̀n sí i lọ́dọọdún ? ”
O wa beere pe : “ Nitori naa , ki lo de ti a o tun le reti ki iwa awon omode maa sunwon si i lodoodun ? ”
Báwo ni igi yìí ṣe máa ń fọ eyín mọ́ ?
Bawo ni igi yii se maa n fo eyin mo ?
▪ Fi Ọ̀wọ̀ Wọn Wọ̀ Wọ́n .
# Fi Owo Won Wo Won .
Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ ni Fílípì , ó mọ Bíbélì dáadáa , ó sì tún máa ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .
Okan lara awon omo eyin Jesu akokobere ni Filipi , o mo Bibeli daadaa , o si tun maa n koni lekoo Bibeli .
Láti ọdún 1879 la ti ń tẹ ìwé ìròyìn yìí déédéé , kì í sì í dá sí ọ̀rọ̀ ìṣèlú .
Lati odun 1879 la ti n te iwe iroyin yii deedee , ki i si i da si oro iselu .
Nítorí náà , o gbọ́dọ̀ sakun láti jẹ́ àpẹẹrẹ rere , yálà bàbá rẹ jẹ́ alàgbà tàbí kì í ṣe alàgbà .
Nitori naa , o gbodo sakun lati je apeere rere , yala baba re je alagba tabi ki i se alagba .
17 , 18 .
17 , 18 .
Jósẹ́fù kò bá Màríà ní ìbálòpọ̀ títí dẹ̀yìn ìgbà tó bímọ .
Josefu ko ba Maria ni ibalopo titi deyin igba to bimo .
Nítorí náà kíkí èrò pé kí ọmọ Léfì tí kì í ṣe àlùfáà wá sun tùràrí níwájú Jèhófà yẹ kó mú káwọn ọlọ̀tẹ̀ náà séra ró , kí ó sì pe orí wọn wálé .
Nitori naa kiki ero pe ki omo Lefi ti ki i se alufaa wa sun turari niwaju Jehofa ye ko mu kawon olote naa sera ro , ki o si pe ori won wale .
A gbọ́dọ̀ “ kọ àìṣòdodo sílẹ̀ ní àkọ̀tán ” ká sì “ yí padà kúrò nínú ohun búburú . ”
A gbodo " ko aisododo sile ni akotan " ka si " yi pada kuro ninu ohun buburu . "
Ìtẹ̀jáde olójú ewé 32 ni ìwé pẹlẹbẹ Kí Ni Ọlọrun Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa ? , kò sì fẹ̀ ju ìwé ìròyìn yìí lọ .
Itejade oloju ewe 32 ni iwe pelebe Ki Ni Olorun N Beere Lowo Wa ? , ko si fe ju iwe iroyin yii lo .
Láàárín àkókò yẹn , alàgbà kan àti ìyàwó rẹ̀ nínú ìjọ tó ń sọ èdè Ṣáìnà yẹn máa ń rìn mọ́ àwa méjèèjì .
Laaarin akoko yen , alagba kan ati iyawo re ninu ijo to n so ede Saina yen maa n rin mo awa mejeeji .
Nígbà táwọn èèyàn fẹ́ mọ̀ nípa ipò Jésù àti ọlá àṣẹ tó ní , ó fi ìgboyà dá wọn lóhùn pé : “ Èmi ní ẹ̀rí tí ó tóbi ju ti Jòhánù [ Olùbatisí ] lọ , nítorí pé àwọn iṣẹ́ náà gan - an tí Baba mi yàn lé mi lọ́wọ́ láti ṣe ní àṣeparí , àwọn iṣẹ́ náà tìkára wọn tí èmi ń ṣe , ń jẹ́rìí nípa mi pé Baba ni ó rán mi wá . ” — Jòhánù 5 : 36 .
Nigba tawon eeyan fe mo nipa ipo Jesu ati ola ase to ni , o fi igboya da won lohun pe : " Emi ni eri ti o tobi ju ti Johanu [ Olubatisi ] lo , nitori pe awon ise naa gan - an ti Baba mi yan le mi lowo lati se ni asepari , awon ise naa tikara won ti emi n se , n jerii nipa mi pe Baba ni o ran mi wa . " -- Johanu 5 : 36 .
Nígbà míì , ọ̀rọ̀ ọmọ títọ́ lè kààyàn láyà .
Nigba mii , oro omo tito le kaayan laya .
Ó tún sọ wí pé:“Ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti àìṣedéédéé wọnlèmi kì yóò sì rántí mọ́.”
O tun so wi pe:"Ese won ati aisedeedee wonlemi ki yoo si ranti mo."
Nígbà tí ó sì ti gbà òkèlè náà tan, ó jáde lójúkan náà àkókò náà si jẹ òru.
Nigba ti o si ti gba okele naa tan, o jade lojukan naa akoko naa si je oru.
Olóró ni wọ́n , oníkèéta ni wọ́n , ẹlẹ́mìí ìgbẹ̀san ni wọ́n , paramọ́lẹ̀ ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ ni wọ́n , apààyàn ni wọ́n , ọmọ èṣù tí í ṣe adánilóró àti oníṣẹ́ ibi ni wọ́n . ”
Oloro ni won , onikeeta ni won , elemii igbesan ni won , paramole ologbon ewe ni won , apaayan ni won , omo esu ti i se adaniloro ati onise ibi ni won . "
Obìnrin náà sì dáhùn ó sì wí pé, Bí ẹ̀mí rẹ ti ń bẹ láàyè, Olúwa mi ọba, kò sí ìyípadà sí ọwọ́ ọ̀tún, tàbí sí ọwọ́ òsì nínú gbogbo èyí tí Olúwa mi ọba ti wí
Obinrin naa si dahun o si wi pe, Bi emi re ti n be laaye, Oluwa mi oba, ko si iyipada si owo otun, tabi si owo osi ninu gbogbo eyi ti Oluwa mi oba ti wi
Mo Bẹ̀rù Ikú , àmọ́ Ìyè “ Lọ́pọ̀ Yanturu ” Ni Mò Ń Retí Báyìí ( P .
Mo Beru Iku , amo Iye " Lopo Yanturu " Ni Mo N Reti Bayii ( P .
Ní ti àwọn ẹni burúkú , a óò ké wọn kúrò lórí ilẹ̀ ayé gan - an ; àti ní ti àwọn aládàkàdekè , a ó fà wọ́n tu kúrò lórí rẹ̀ . ”
Ni ti awon eni buruku , a oo ke won kuro lori ile aye gan - an ; ati ni ti awon aladakadeke , a o fa won tu kuro lori re . "
That is what a husband in Mexico named Adrián did .
That is what a husband in Mexico named Adrian did .
Bákan náà , Róòmù 5 : 3 - 5 sọ fún wa pé : “ Ẹ jẹ́ kí a máa yọ ayọ̀ ńláǹlà nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú , níwọ̀n bí a ti mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá ; ìfaradà , ní tirẹ̀ , ipò ìtẹ́wọ́gbà ; ipò ìtẹ́wọ́gbà , ní tirẹ̀ , ìrètí , ìrètí náà kì í sì í ṣamọ̀nà sí ìjákulẹ̀ . ”
Bakan naa , Roomu 5 : 3 - 5 so fun wa pe : " E je ki a maa yo ayo nlanla nigba ti a ba wa ninu iponju , niwon bi a ti mo pe iponju n mu ifarada wa ; ifarada , ni tire , ipo itewogba ; ipo itewogba , ni tire , ireti , ireti naa ki i si i samona si ijakule . "
“ Òmìnira Ológo ” Ti Fẹ́rẹ̀ẹ́ Dé !
" Ominira Ologo " Ti Feree De !
Onísáàmù kan sọ pé : “ Bí ó bá ṣẹlẹ̀ pé baba mi àti ìyá mi fi mí sílẹ̀ , àní Jèhófà tìkára rẹ̀ yóò tẹ́wọ́ gbà mí . ” — Sáàmù 27 : 10 .
Onisaamu kan so pe : " Bi o ba sele pe baba mi ati iya mi fi mi sile , ani Jehofa tikara re yoo tewo gba mi . " -- Saamu 27 : 10 .
Wòlíì náà dáhùn pé, Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti ń bẹ láàyè, ẹni tí mo ń sìn, èmi kò ní gba ohun kan, Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Námánì rọ̀ ọ́ láti gbàá, ó kọ̀
Wolii naa dahun pe, Gege bi Oluwa ti n be laaye, eni ti mo n sin, emi ko ni gba ohun kan, Bi o tile je pe Namani ro o lati gbaa, o ko
Nítorí náà , àwọn méjèèjì ló nílò ìrànlọ́wọ́ . ”
Nitori naa , awon mejeeji lo nilo iranlowo . "
Èrò tí kò dáa wo làwọn kan ní nípa ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ń dá ?
Ero ti ko daa wo lawon kan ni nipa ese ti won n da ?
Gbogbo àwọn tí ó rí mí fi mí ṣe ẹlẹ́yà;wọ́n yọ ètè ẹ̀gàn wọn sí mi, wọ́n sì ń mi orí wọn pé.
Gbogbo awon ti o ri mi fi mi se eleya;won yo ete egan won si mi, won si n mi ori won pe.
“ Àwọn Ẹlẹ́rìí tó jẹ́ ẹni ọ̀wọ́n yìí ló ń mú ipò iwájú nínú wíwàásù láwọn àgbègbè tó jẹ́ àdádó , àwọn ló ń ṣèrànwọ́ láti dá àwọn ìjọ tuntun sílẹ̀ , tí wọ́n sì ń jẹ́ káwọn arákùnrin àti arábìnrin tó wà níbẹ̀ dàgbà nípa tẹ̀mí . ”
“ Awon Elerii to je eni owon yii lo n mu ipo iwaju ninu wiwaasu lawon agbegbe to je adado , awon lo n seranwo lati da awon ijo tuntun sile , ti won si n je kawon arakunrin ati arabinrin to wa nibe dagba nipa temi . ”
Nígbà tí wọ́n súnmọ́ Jerusalẹmu, tí wọ́n dé Bẹtifage ní Òkè Olifi, Jesu rán àwọn ọmọ-ẹ̀yìn meji lọ ṣiwaju.
Nigba ti won sunmo Jerusalemu, ti won de Betifage ni Oke Olifi, Jesu ran awon omo-eyin meji lo siwaju.
Dada ti ṣe ifihan ninu ọpọlọpọ ere tẹlifisiọnu, to fi mọ awọn ere EbonylifeTv bii Married to the Game,[1] Best Friends ati Dere, ere ti n ṣe aṣamubadọgba “Cinderella“ ti Disney ni ilẹ Afirika.[2] O tun kopa ninu ere tẹlifisiọnu Mnet ti akọle re jẹ Jemeji, o si ti ni awọn ipa ninu Tinsel, So Wrong so Wright, Needles Eyes, Bella’s Place ati awọn miiran.[1]
Dada ti se ifihan ninu opolopo ere telifisionu, to fi mo awon ere EbonylifeTv bii Married to the Game,[1] Best Friends ati Dere, ere ti n se asamubadogba "Cinderella" ti Disney ni ile Afirika.[2] O tun kopa ninu ere telifisionu Mnet ti akole re je Jemeji, o si ti ni awon ipa ninu Tinsel, So Wrong so Wright, Needles Eyes, Bella's Place ati awon miiran.[1]
Ẹ lè wá rí i pé á túbọ̀ rọrùn fáwọn ọmọ yín láti lóye àwọn òfin tẹ́ ẹ fún wọn , wọ́n á sì máa tẹ̀ lé e .
E le wa ri i pe a tubo rorun fawon omo yin lati loye awon ofin te e fun won , won a si maa te le e .
Níbẹ̀ , mo ṣiṣẹ́ ní Ẹ̀ka Ìkówèéránṣẹ́ àti Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ìsìn .
Nibe , mo sise ni Eka Ikoweeranse ati Eka Ise Isin .
A gbọ́dọ̀ máa padà lọ bẹ àwọn èèyàn wọ̀nyí wò , ká máa dáhùn onírúurú ìbéèrè tí wọ́n bá ní . . . , ká sì wá bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ àwòkọ́ṣe . . . gbàrà tí àǹfààní rẹ̀ bá ti yọ . ”
A gbodo maa pada lo be awon eeyan wonyi wo , ka maa dahun oniruuru ibeere ti won ba ni . . . , ka si wa bere ikekoo awokose . . . gbara ti anfaani re ba ti yo . "
Bí mo ṣe ya ọmọ ìgboro láti kékeré nìyẹn .
Bi mo se ya omo igboro lati kekere niyen .
Wọ́n fi sinimá yìí han àwọn èèyàn ní orílẹ̀ - èdè Austria , Jámánì , Luxemburg àti Switzerland àti ní gbogbo ibi tí wọ́n ti ń sọ èdè Jámánì kárí ayé .
Won fi sinima yii han awon eeyan ni orile - ede Austria , Jamani , Luxemburg ati Switzerland ati ni gbogbo ibi ti won ti n so ede Jamani kari aye .
Sì kíyèsĩ, àwọn ogun wọn
Si kiyesi, awon ogun won
Ọ̀pọ̀ èèyàn lónìí fara mọ́ èrò àwọn olókìkí èèyàn yẹn , wọ́n ń sọ pé kìkì ohun táwọn bá rí làwọn máa gbà gbọ́ .
Opo eeyan lonii fara mo ero awon olokiki eeyan yen , won n so pe kiki ohun tawon ba ri lawon maa gba gbo .
Ìgbà mìíràn wà tí wọ́n máa ń bi mí pé , “ Kí lo máa ṣe nígbà tó o bá dàgbà , ìwọ tó ò nílé tiẹ̀ fúnra ẹ̀ tí wọn ò sì ní fún ọ lówó ìfẹ̀yìntì . ”
Igba miiran wa ti won maa n bi mi pe , " Ki lo maa se nigba to o ba dagba , iwo to o nile tie funra e ti won o si ni fun o lowo ifeyinti . "
Ìwé kan tó ń jẹ Encyclopedia of Religion and Ethics sọ pé : “ Àwọn ọmọlẹ́yìn Jésù gbà pé ikú dà bí oorun , sàréè sì jẹ́ ibi tí àwọn olóòótọ́ tó ti kú ti ń sinmi . ” *
Iwe kan to n je Encyclopedia of Religion and Ethics so pe : " Awon omoleyin Jesu gba pe iku da bi oorun , saree si je ibi ti awon oloooto to ti ku ti n sinmi . " *
mitiredati
mitiredati
Wọ́n sọ fún Jèhófà pé inú àwọn dùn pé ọmọ àwọn ti ya ara rẹ̀ sí mímọ́ fún un . ”
Won so fun Jehofa pe inu awon dun pe omo awon ti ya ara re si mimo fun un . "
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀ , inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun , la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò .
Ba o ba fi han pe o yato , inu Iwe Mimo ni Itumo Aye Tuntun , la ti mu gbogbo ese Iwe Mimo ta a lo .
Ṣé Àwọn Míì Wà Lára Wọn ?
Se Awon Mii Wa Lara Won ?
Lẹsẹkẹsẹ ni àwọn onigbagbọ bá ṣe ètò fún Paulu láti lọ sí èbúté. Ṣugbọn Sila ati Timoti dúró ní Beria.
Lesekese ni awon onigbagbo ba se eto fun Paulu lati lo si ebute. Sugbon Sila ati Timoti duro ni Beria.
Ní ìbámu pẹ̀lú ìfẹ́ Jèhófà , ọdún tó tẹ̀ lé e ni àwọn Júù tó pa dà sílé láti ìgbèkùn yìí fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì tuntun lélẹ̀ .
Ni ibamu pelu ife Jehofa , odun to te le e ni awon Juu to pa da sile lati igbekun yii fi ipile tenpili tuntun lele .
kohaṣepe
kohasepe
Bàbá mi kọ̀wé sí ẹ̀ka ọ́fíìsì àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Belgium ó sì bẹ̀ wọ́n pé kí wọ́n wá mi kàn kí wọ́n sì gbìyànjú láti máa kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .
Baba mi kowe si eka ofiisi awa Elerii Jehofa ni Belgium o si be won pe ki won wa mi kan ki won si gbiyanju lati maa ko mi lekoo Bibeli .
Ṣé Gbogbo Èèyàn Rere Ló Ń Lọ sí Ọ̀run ?
Se Gbogbo Eeyan Rere Lo N Lo si Orun ?
Ó ní, “Lílọ ni à ń lọ sí Jerusalẹmu yìí, a óo fi Ọmọ-Eniyan lé àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin lọ́wọ́. Wọn yóo dá a lẹ́bi ikú, wọn yóo sì fi lé àwọn tí kì í ṣe Juu lọ́wọ́.
O ni, “Lilo ni a n lo si Jerusalemu yii, a oo fi Omo-Eniyan le awon olori alufaa ati awon amofin lowo. Won yoo da a lebi iku, won yoo si fi le awon ti ki i se Juu lowo.
Àwọn ará Síríà gba ìpínlẹ̀ mọ́ Gílíádì lọ́wọ́ , ìyẹn àgbègbè Ísírẹ́lì níhà ìlà oòrùn Odó Jọ́dánì , wọ́n sì ṣe àwọn èèyàn Ọlọ́run tó ń gbé níbẹ̀ léṣe gan - an .
Awon ara Siria gba ipinle mo Giliadi lowo , iyen agbegbe Isireli niha ila oorun Odo Jodani , won si se awon eeyan Olorun to n gbe nibe lese gan - an .
Kí nìdí ?
Ki nidi ?