diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
kò sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, mo sì ń ranti yín ninu adura mi.
ko sinmi lati maa dupe nitori yin, mo si n ranti yin ninu adura mi.
Ní oṣù February kan báyìí , ọ̀gá tó ti fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ yìí rin ìrìn àjò ọgọ́jọ [ 160 ] kìlómítà lọ sí ilé ọmọ rẹ̀ ní ìlú Nakuru tó wà ní Àfonífojì Ńlá .
Ni osu February kan bayii , oga to ti feyin ti lenu ise yii rin irin ajo ogojo [ 160 ] kilomita lo si ile omo re ni ilu Nakuru to wa ni Afonifoji Nla .
Ìwé náà , Mexico’s Feasts of Life , ṣàlàyé pé : Àkókò posadas ti tó , ọjọ́ mẹ́sàn - án tó wà fún idán pípa tó sì máa jálẹ̀ sí Alẹ́ tó Ṣáájú Kérésìmesì , èyí tó ń ránni létí bí Jósẹ́fù àti Màríà ṣe ń dá nìkan rìn kiri nínú ìlú ńlá Bẹ́tílẹ́hẹ́mù , àti ìgbà tí wọ́n rí inúrere àti ibì kan láti wọ̀ sí .
Iwe naa , Mexico’s Feasts of Life , salaye pe : Akoko posadas ti to , ojo mesan - an to wa fun idan pipa to si maa jale si Ale to Saaju Keresimesi , eyi to n ranni leti bi Josefu ati Maria se n da nikan rin kiri ninu ilu nla Betilehemu , ati igba ti won ri inurere ati ibi kan lati wo si .
Nígbà yẹn , mi ò tíì mọ bí ayọ̀ téèyàn máa ń rí nínú sísọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn Jésù Kristi ṣe máa ń pọ̀ tó .
Nigba yen , mi o tii mo bi ayo teeyan maa n ri ninu siso awon eeyan di omo eyin Jesu Kristi se maa n po to .
Ní nǹkan bí ẹgbàá [ 2,000 ] ọdún ó lé díẹ̀ sẹ́yìn , Ọlọ́run rán Ọ̀rọ̀ náà wá sáyé gẹ́gẹ́ bí ẹni pípé , ó sì fòótọ́ inú ṣe ìfẹ́ Baba rẹ̀ .
Ni nnkan bi egbaa [ 2,000 ] odun o le die seyin , Olorun ran Oro naa wa saye gege bi eni pipe , o si footo inu se ife Baba re .
Kí èyí má ṣe yà yín lẹ́nu
Ki eyi ma se ya yin lenu
Ẹni tuntun náà lè dara pọ̀ mọ́ wa nínú iṣẹ́ ìkórè náà , a sì lè jàǹfààní lára tiẹ̀ náà lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù . ​ — Jòh . 4 : ​ 36 - 38 .
Eni tuntun naa le dara po mo wa ninu ise ikore naa , a si le janfaani lara tie naa lenu ise iwaasu . ​ — Joh . 4 : ​ 36 - 38 .
Máa rán àwọn eniyan létí nípa nǹkan wọnyi. Kìlọ̀ fún wọn níwájú Ọlọrun pé kí wọn má máa jiyàn lórí oríṣìíríṣìí ọ̀rọ̀ tí kò wúlò, tíí sìí máa da àwọn tí ó bá gbọ́ lọ́kàn rú.
Maa ran awon eniyan leti nipa nnkan wonyi. Kilo fun won niwaju Olorun pe ki won ma maa jiyan lori orisiirisii oro ti ko wulo, tii sii maa da awon ti o ba gbo lokan ru.
Ìyàwó rẹ̀ á mọrírì irú ìrànlọ́wọ́ bẹ́ẹ̀ gan - an ni . — Éfésù 5 : 25 , 28 , 29 .
Iyawo re a moriri iru iranlowo bee gan - an ni . — Efesu 5 : 25 , 28 , 29 .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 12 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 12 ]
Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ láti forí ti nǹkan ni pé kí a gbé góńgó kan tó ní láárí , tí ọwọ́ wá sì lè tẹ̀ kalẹ̀ .
Igbese akoko lati fori ti nnkan ni pe ki a gbe gongo kan to ni laari , ti owo wa si le te kale .
ni fún Un! Ẹni to tô fún Ara Rẹ̀
ni fun Un! Eni to to fun Ara Re
Póòpù Benedict Kẹrìndínlógún rọ àwọn arìnrìn - àjò náà pé kí wọ́n di “ ẹ̀yà ìran tuntun ti àwọn àpọ́sítélì ” bó sì ṣe ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ nìṣó , ó rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n tan “ Ìhìn Rere kálẹ̀ láàárín àwọn ará , ọ̀rẹ́ àti gbogbo àwọn tí wọ́n bá ń bá pàdé . ”
Poopu Benedict Kerindinlogun ro awon arinrin - ajo naa pe ki won di “ eya iran tuntun ti awon apositeli ” bo si se n ba oro re niso , o ro won pe ki won tan “ Ihin Rere kale laaarin awon ara , ore ati gbogbo awon ti won ba n ba pade . ”
Nítorí pẹlu ọpọlọpọ ìdààmú ati ọkàn wúwo ni mo fi kọ ọ́, kì í ṣe pé kí ó lè bà yín lọ́kàn jẹ́ ṣugbọn kí ẹ lè mọ̀ pé ìfẹ́ tí mo ní si yín pọ̀ pupọ.
Nitori pelu opolopo idaamu ati okan wuwo ni mo fi ko o, ki i se pe ki o le ba yin lokan je sugbon ki e le mo pe ife ti mo ni si yin po pupo.
Má ṣe jẹ́ kí àwọn ohun tí kò ní láárí gba àkókò rẹ , kàkà bẹ́ẹ̀ , ńṣe ni kó o máa fi àkókò yìí ran àwọn ẹlòmíì lọ́wọ́ .
Ma se je ki awon ohun ti ko ni laari gba akoko re , kaka bee , nse ni ko o maa fi akoko yii ran awon elomii lowo .
Pọ́ọ̀lù ti wá mọ̀ pé tí òun kò bá fẹ́ máa kábàámọ̀ àwọn nǹkan tó kù díẹ̀ káàtó tí òun ti ṣe sẹ́yìn , àfi kí òun máa sa gbogbo ipá òun lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Ọlọ́run .
Poolu ti wa mo pe ti oun ko ba fe maa kabaamo awon nnkan to ku die kaato ti oun ti se seyin , afi ki oun maa sa gbogbo ipa oun lenu ise isin Olorun .
Ọ̀pọ̀ ló gbà pé , èdè Hébérù ni àpọ́sítélì Mátíù kọ́kọ́ fi kọ ìwé Ìhìn Rere rẹ̀ .
Opo lo gba pe , ede Heberu ni apositeli Matiu koko fi ko iwe Ihin Rere re .
Bíi ti Ámósì àtàwọn ọmọlẹ́yìn Jésù ìjímìjí , pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Jèhófà , àwa náà ń fìgboyà sọ̀rọ̀ Rẹ̀ .
Bii ti Amosi atawon omoleyin Jesu ijimiji , pelu iranlowo Jehofa , awa naa n figboya soro Re .
Ayọ̀ tó kún inú mi níbẹ̀rẹ̀ yẹn ti di ọ̀nà ìgbésí ayé fún mi .
Ayo to kun inu mi nibere yen ti di ona igbesi aye fun mi .
Kódà ní alẹ́ tí ewu pé ọ̀tá lè gbéjà koni lójijì máa ń pọ̀ jù lọ pàápàá , ẹ̀rù kì í ba Dáfídì láti sùn .
Koda ni ale ti ewu pe ota le gbeja koni lojiji maa n po ju lo paapaa , eru ki i ba Dafidi lati sun .
díẹ̀ sì ṣubú nínú àwọn ènìyàn náà nínú àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì, Ùráyà ará Hítì sì kú pẹ̀lú
die si subu ninu awon eniyan naa ninu awon iranse Dafidi, Uraya ara Hiti si ku pelu
hasieli
hasieli
Rárá o , nítorí pé ìwé ìròyìn Kiplinger’s Personal Finance sọ pé : “ Nínú àwọn ipò kan , ìwádìí wa fi hàn pé àwọn ìpínlẹ̀ tí kì í gba owó orí lórí iye tó ń wọlé fúnni máa ń gba owó orí tó ga lórí dúkìá , lórí ọjà àtàwọn owó orí mìíràn . ”
Rara o , nitori pe iwe iroyin Kiplinger's Personal Finance so pe : " Ninu awon ipo kan , iwadii wa fi han pe awon ipinle ti ki i gba owo ori lori iye to n wole funni maa n gba owo ori to ga lori dukia , lori oja atawon owo ori miiran . "
Èṣo àjàrà wọn kún fún oró, Ìdì wọn korò
Eso ajara won kun fun oro, Idi won koro
Àwọn Kristẹni òbí máa ń wo àwọn ọmọ wọn gẹ́gẹ́ bí ohun tí Jèhófà fún wọn ṣọ́ , ojú rẹ̀ sì ni wọ́n ń wò fún ìrànlọ́wọ́ láti tọ́ wọn dàgbà .
Awon Kristeni obi maa n wo awon omo won gege bi ohun ti Jehofa fun won so , oju re si ni won n wo fun iranlowo lati to won dagba .
Báwo lẹnì kan ṣe lè máa ṣọ̀fọ̀ kí inú rẹ̀ sì tún máa dùn ?
Bawo leni kan se le maa sofo ki inu re si tun maa dun ?
Wọ́n sọ pé : Bó ṣe yẹ kó rí náà nìyẹn . . . .
Won so pe : Bo se ye ko ri naa niyen . . . .
Wọn ò lè dá a ṣe .
Won o le da a se .
Ìwọ mú ọjọ́ Ìsinmi rẹ mímọ́ di mímọ̀ fún wọn, o sì fún wọn ní àwọn ìlànà, àwọn àṣẹ àti àwọn òfin láti ọwọ́ọ Mósè ìránṣẹ́ẹ̀ rẹ
Iwo mu ojo Isinmi re mimo di mimo fun won, o si fun won ni awon ilana, awon ase ati awon ofin lati owoo Mose iransee re
nígbà tí ẹ bá n dà wọn padà sílé
nigba ti e ba n da won pada sile
Ká ní pé Ádámù àti Éfà jẹ́ kí Jèhófà máa ṣàkóso àwọn lọ ni , wọn ì bá máa gbé lórí ilẹ̀ ayé tó jẹ́ Párádísè títí láé . — Jẹ́nẹ́sísì 2 : 15 - 17 .
Ka ni pe Adamu ati Efa je ki Jehofa maa sakoso awon lo ni , won i ba maa gbe lori ile aye to je Paradise titi lae . -- Jenesisi 2 : 15 - 17 .
Báwo ni a ó ṣe lè fara dà á tó bá tún lọ jù báyìí lọ ?
Bawo ni a o se le fara da a to ba tun lo ju bayii lo ?
Kò níṣẹ́ méjì ju kó máa tan ìwà àìṣòdodo kálẹ̀ lọ .
Ko nise meji ju ko maa tan iwa aisododo kale lo .
Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ tó wà nínú Mátíù 26 : 41 ti fi hàn , tàánútàánú ni Jésù fi jẹ́ ká mọ̀ pé òún lóye àwọn kùdìẹ̀ - kudiẹ ẹ̀dá èèyàn .
Gege bi akosile to wa ninu Matiu 26 : 41 ti fi han , taanutaanu ni Jesu fi je ka mo pe oun loye awon kudie - kudie eda eeyan .
Komsomolskaya Pravda , ìwé ìròyìn kan lédè Rọ́ṣíà tí ìpíndọ́gba rẹ̀ tó ọgọ́ta ọ̀kẹ́ [ 1,200,000 ] , sọ nínú ìtẹ̀jáde rẹ̀ ti November 21 , 1998 pé : “ Láàárín ọdún méjì péré , Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ilẹ̀ Rọ́ṣíà ṣe ìwé tó lé ní mẹ́wàá , ìwé pẹlẹbẹ , àtàwọn ìwé ìléwọ́ ‘ nítorí ’ àwọn Oní - Jèhófà . ”
Komsomolskaya Pravda , iwe iroyin kan lede Rosia ti ipindogba re to ogota oke [ 1,200,000 ] , so ninu itejade re ti November 21 , 1998 pe : " Laaarin odun meji pere , Soosi Otodoosi Ile Rosia se iwe to le ni mewaa , iwe pelebe , atawon iwe ilewo ' nitori ' awon Oni - Jehofa . "
O sọ wá di ẹni àmúpòwe láàrin àwọn orílẹ̀-èdè,ati ẹni yẹ̀yẹ́ láàrin gbogbo ayé.
O so wa di eni amupowe laarin awon orile-ede,ati eni yeye laarin gbogbo aye.
[ Àwọn Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ]
[ Awon Alaye isale iwe ]
Ohun Tó Lè Mú Kí Èèyàn Túbọ̀ Láyọ̀
Ohun To Le Mu Ki Eeyan Tubo Layo
Bí Jósẹ́fù ṣe wọlé ni obìnrin yìí pa kuuru mọ́ ọn , ó dì í lẹ́wù mú , ó sì tún bẹ̀rẹ̀ sí i bẹ̀ ẹ́ pé : “ Sùn tì mí ! ”
Bi Josefu se wole ni obinrin yii pa kuuru mo on , o di i lewu mu , o si tun bere si i be e pe : “ Sun ti mi ! ”
Ó ní láti jẹ́ pé ibẹ̀ ló ń sùn sí .
O ni lati je pe ibe lo n sun si .
Wọ́n kọ́ àwọn ilé kan ní alágbèékà kan tàbí alágbèékà méjì ( 5 ) àwọn míì sì wà nínú ọgbà tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ .
Won ko awon ile kan ni alagbeeka kan tabi alagbeeka meji ( 5 ) awon mii si wa ninu ogba ti won se losoo .
Bí Àwọn Ọ̀dọ́ Ṣe Lè Rí Ìrànlọ́wọ́
Bi Awon Odo Se Le Ri Iranlowo
Kò rọrùn o , àmọ́ mi ò fi iṣẹ́ aṣáájú ọ̀nà sílẹ̀ .
Ko rorun o , amo mi o fi ise asaaju ona sile .
nítorí tí wọ́n kọ̀ sílẹ̀ àti nítorí pé wọ́n ń sin Baali àti Aṣtoreti.
nitori ti won ko sile ati nitori pe won n sin Baali ati Astoreti.
Nítorí náà, ẹ má ṣe tún jẹ́ kí a máa dá ara wa lẹ́jọ́ mọ́. Ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀, ẹ pinu nínú ọkàn yín láti má ṣe fi ohun ìkọ̀sẹ̀ tàbí òkúta ìdìgbòlù kankan sí ọ̀nà arákùnrin tàbí arábìnrin yín.
Nitori naa, e ma se tun je ki a maa da ara wa lejo mo. Sugbon dipo bee, e pinu ninu okan yin lati ma se fi ohun ikose tabi okuta idigbolu kankan si ona arakunrin tabi arabinrin yin.
Sonia rọ lápá rọ lẹ́sẹ̀ , ó sì ṣeé ṣe kó jẹ́ pé iṣẹ́ àṣekúdórógbó tó ń ṣe ló fà á .
Sonia ro lapa ro lese , o si see se ko je pe ise asekudorogbo to n se lo fa a .
Ní àwọn ìlú ńláńlá àti ìlú kéékèèké jákèjádò Kánádà ló ti ń sọ àsọyé , tó sì ń fi sinimá àti àwòrán ara ògiri táa mọ̀ sí “ Photo - Drama of Creation ” [ “ Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Onífọ́tò Nípa Ìṣẹ̀dá ” ] hàn .
Ni awon ilu nlanla ati ilu keekeeke jakejado Kanada lo ti n so asoye , to si n fi sinima ati aworan ara ogiri taa mo si “ Photo - Drama of Creation ” [ “ Awokekoo Onifoto Nipa Iseda ” ] han .
àwọn orílẹ̀ èdè àyíká rẹ náà yóò jìyà ìfiṣẹ̀sín
awon orile ede ayika re naa yoo jiya ifisesin
Wọ́n ta àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ eré náà fáwọn èèyàn , ìyẹn àwọn nǹkan bí ike ìjẹun , ife ìmumi , àwọn ohun ọ̀ṣọ́ , aṣọ , ẹ̀wọ̀n tí wọ́n ń so kọ́kọ́rọ́ mọ́ , agogo , àtùpà àti ayò , àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ .
Won ta awon nnkan to je mo ere naa fawon eeyan , iyen awon nnkan bi ike ijeun , ife imumi , awon ohun oso , aso , ewon ti won n so kokoro mo , agogo , atupa ati ayo , ati bee bee lo .
Nígbà náà ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bá ara wọn jiyàn pé, “Bí a bá wí pé, ‘Láti ọ̀run ni,’ yóo sọ pé, ‘Kí ló dé tí ẹ kò fi gbà á gbọ́?’
Nigba naa ni won bere si ba ara won jiyan pe, "Bi a ba wi pe, 'Lati orun ni,' yoo so pe, 'Ki lo de ti e ko fi gba a gbo?'
Báwo ni inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí ṣe kan àdúrà ?
Bawo ni inu rere ailetoosi se kan adura ?
Kí nìdí tí èyí fi ṣe pàtàkì ?
Ki nidi ti eyi fi se pataki ?
Àmọ́ , kò sí ẹ̀rí tó fi hàn pé àwọn Kristẹni ọ̀rúndún kìíní ṣe bẹ́ẹ̀ .
Amo , ko si eri to fi han pe awon Kristeni orundun kiini se bee .
Ní báyìí , mo ní àwọn ẹni ọ̀wọ́n tá a jọ ń sin Jèhófà . ”
Ni bayii , mo ni awon eni owon ta a jo n sin Jehofa . ”
Lẹ́yìn tó ti ka 2 Kọ́ríńtì 7 : 1 tó sì ti fẹnu ara ẹ̀ jẹ́wọ́ pé “ ẹ̀gbin ti ẹran ara ” ni àṣà náà já sí lójú Ọlọ́run , ó pinnu pé òun ò ní fẹnu kan sìgá mọ́ .
Leyin to ti ka 2 Korinti 7 : 1 to si ti fenu ara e jewo pe " egbin ti eran ara " ni asa naa ja si loju Olorun , o pinnu pe oun o ni fenu kan siga mo .
Àní sẹ́ , Jèhófà lágbára láti mọ ohun tá à ń rò , ohun tó ń sún wa ṣe nǹkan àti ohun tí ọkàn wa ń fẹ́ .
Ani se , Jehofa lagbara lati mo ohun ta a n ro , ohun to n sun wa se nnkan ati ohun ti okan wa n fe .
Nígbà tí Pọ́ọ̀lù sọ pé , ẹ “ Máa fi ire ṣẹ́gun ibi , ” ìyẹn ò túmọ̀ sí pé kí Kristẹni kan wá gbàgbàkugbà láyè torí ẹ̀sìn .
Nigba ti Poolu so pe , e “ Maa fi ire segun ibi , ” iyen o tumo si pe ki Kristeni kan wa gbagbakugba laye tori esin .
Ṣugbọn àwọn kan ninu wọn ń sọ pé, “Agbára Beelisebulu, olórí àwọn ẹ̀mí èṣù, ni ó fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.”
Sugbon awon kan ninu won n so pe, “Agbara Beelisebulu, olori awon emi esu, ni o fi n le awon emi esu jade.”
Bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ , tá a bá ní ká wọn iye wúrà , ìyẹn góòlù , tí Hírámù ọba ìlú Tírè fi ránṣẹ́ sí Sólómọ́nì , ó máa wúwo tó ọgọ́rin [ 80 ] àpò sìmẹ́ǹtì , iye yẹn náà sì ni ọbabìnrin Ṣébà fi ránṣẹ́ sí i , iye wúrà tí wọ́n sì kó wọlé fún Sólómọ́nì fúnra rẹ̀ láti ìlú Ófírì wúwo ju ọgọ́rùn - ún mẹ́ta [ 300 ] àpò sìmẹ́ǹtì lọ .
Bi Iwe Mimo se so , ta a ba ni ka won iye wura , iyen goolu , ti Hiramu oba ilu Tire fi ranse si Solomoni , o maa wuwo to ogorin [ 80 ] apo simenti , iye yen naa si ni obabinrin Seba fi ranse si i , iye wura ti won si ko wole fun Solomoni funra re lati ilu Ofiri wuwo ju ogorun - un meta [ 300 ] apo simenti lo .
Àmọ́ lọ́dún 1990 , ó bẹ̀rẹ̀ sí í yí èrò rẹ̀ pa dà .
Amo lodun 1990 , o bere si i yi ero re pa da .
Èyí béèrè fún àkọsílẹ̀ ìlà ìdílé tó pé pérépéré láti mọ àwọn tí ogún tọ́ sí àti láti rí i dájú pé kìkì àwọn tó lẹ́tọ̀ọ́ láti di àlùfáà la fún ní ipò náà .
Eyi beere fun akosile ila idile to pe perepere lati mo awon ti ogun to si ati lati ri i daju pe kiki awon to letoo lati di alufaa la fun ni ipo naa .
Nígbà tí wọ́n ń fi gbogbo àyíká hàn wọ́n , ìyàwó dókítà náà béèrè ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbéèrè nínú Bíbélì .
Nigba ti won n fi gbogbo ayika han won , iyawo dokita naa beere opolopo ibeere ninu Bibeli .
Ìyẹn ni ìwé ìròyìn Jí !
Iyen ni iwe iroyin Ji !
Kí Jéésù ô bá ni mú ìgbà tô dùn wá
Ki Jeesu o ba ni mu igba to dun wa
Kí Ló Mú Kí Mósè Bínú sí Àwọn Ọmọ Áárónì ? , 2 / 15
Ki Lo Mu Ki Mose Binu si Awon Omo Aaroni ? , 2 / 15
Mọ̀ pé ọkàn irú ẹni bẹ́ẹ̀ ti wọ́, ó ń dá ẹ̀ṣẹ̀, ó sì ń dá ara rẹ̀ lẹ́bi.
Mo pe okan iru eni bee ti wo, o n da ese, o si n da ara re lebi.
Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, bí wọ́n ti ń kọjá lọ, wọ́n rí igi ọ̀pọ̀tọ́ tí Jesu fi bú. Wọ́n rí i pé ó ti gbẹ tigbòǹgbò tigbòǹgbò.
Ni owuro ojo keji, bi won ti n koja lo, won ri igi opoto ti Jesu fi bu. Won ri i pe o ti gbe tigbongbo tigbongbo.
Tó o bá jẹ́ òbí , ohun tí Mánóà bẹ̀bẹ̀ fún yẹn ò lè ṣàjèjì sí ẹ .
To o ba je obi , ohun ti Manoa bebe fun yen o le sajeji si e .
Ìwọ ti sọ àwọn oníṣòwò rẹ di púpọ̀títí wọn yóò fi pọ̀ ju ìràwọ̀ ojú ọ̀run lọṢùgbọ́n bi eṣú ni wọn yóò sọ ilẹ̀ náà di ahoro, wọn yóò sì fò lọ.
Iwo ti so awon onisowo re di pupotiti won yoo fi po ju irawo oju orun loSugbon bi esu ni won yoo so ile naa di ahoro, won yoo si fo lo.
Wákàtí kan àti ìṣẹ́jú márùndínláàdọ́ta
Wakati kan ati iseju marundinlaadota
kejì olórin ìgbàlódé bíi onífujì
keji olorin igbalode bii onifuji
Wọ́n ṣọ̀kan nínú ìgbàgbọ́ wọn nípa irú ẹni tí Ọlọ́run jẹ́ àti ohun tó ń béèrè pé kí wọ́n máa ṣe .
Won sokan ninu igbagbo won nipa iru eni ti Olorun je ati ohun to n beere pe ki won maa se .
Àmọ́ , Jèhófà Ọlọ́run ńkọ́ ?
Amo , Jehofa Olorun nko ?
Ǹjẹ́ O Rántí ?
Nje O Ranti ?
Ta ni Ọlọrun bí kò ṣe OLUWA?Ta sì ni àpáta ààbò bí kò ṣe Ọlọrun wa?
Ta ni Olorun bi ko se OLUWA?Ta si ni apata aabo bi ko se Olorun wa?
mọ̀-ọ́n-mọ̀
mo-on-mo
Kọjá ẹnu ibodè Efraimu ibodè Jeṣana, ẹnu ibodè ẹja, ilé ìṣọ́ Hananeli àti ilé ìṣọ́ ọgọ́rùn-ún, títí dé ẹnu ibodè àgùntàn. Wọ́n sì dúró ní ibodè ìṣọ́.
Koja enu ibode Efraimu ibode Jesana, enu ibode eja, ile iso Hananeli ati ile iso ogorun-un, titi de enu ibode aguntan. Won si duro ni ibode iso.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé iṣẹ́ “ àwọn ọkùnrin tí ń ṣe àbójútó ” àti “ àwọn ìríjú ” yàtọ̀ pátápátá sí tàwọn akọ́nilẹ́kọ̀ọ́ , ohun kan náà ni Pọ́ọ̀lù ń fi wọ́n ṣàlàyé .
Bo tile je pe ise “ awon okunrin ti n se abojuto ” ati “ awon iriju ” yato patapata si tawon akonilekoo , ohun kan naa ni Poolu n fi won salaye .
tí Ò fẹ.
ti O fe.
Ìwọ wí pé, “Mo yan àkókò ìyàsọ́tọ̀;Èmi ni ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ òdodo.
Iwo wi pe, "Mo yan akoko iyasoto;Emi ni eni ti n se idajo ododo.
Báwo la ṣe lè máa bá ara wa sọ̀rọ̀ tàbí hùwà sí ara wa tó máa fi hàn pé a bọ̀wọ̀ fún ara wa ?
Bawo la se le maa ba ara wa soro tabi huwa si ara wa to maa fi han pe a bowo fun ara wa ?
Àbí ẹ ò rí nǹkan , rírí tí Pọ́ọ̀lù rí àwọn arákùnrin tí wọ́n ti sa gbogbo ipá wọn láti rin ìrìn tó jìn tó yẹn jẹ́ orísun okun àti ìtùnú fún un !
Abi e o ri nnkan , riri ti Poolu ri awon arakunrin ti won ti sa gbogbo ipa won lati rin irin to jin to yen je orisun okun ati itunu fun un !
Kí ni Bíbélì sọ fún wa nípa àwọn áńgẹ́lì ?
Ki ni Bibeli so fun wa nipa awon angeli ?
Àwọn ọmọ Sebuluni kò lé àwọn tí wọ́n ń gbé ìlú Kitironi jáde, ati àwọn tí ó ń gbé Nahalali, ṣugbọn àwọn ará Kenaani ń bá wọn gbé, àwọn ọmọ Sebuluni sì ń fi tipátipá kó wọn ṣiṣẹ́.
Awon omo Sebuluni ko le awon ti won n gbe ilu Kitironi jade, ati awon ti o n gbe Nahalali, sugbon awon ara Kenaani n ba won gbe, awon omo Sebuluni si n fi tipatipa ko won sise.
Àwọn ọmọbinrin náà dá wọn lóhùn pé, “Ó wà ní ìlú. Ó ṣẹ̀ṣẹ̀ kọjá nisinsinyii ni. Bí ó ti ń wọ ìlú bọ̀ tààrà nìyí, ẹ yára lọ bá a. Àwọn eniyan ní ẹbọ kan tí wọn óo rú ní orí òkè lónìí.
Awon omobinrin naa da won lohun pe, "O wa ni ilu. O sese koja nisinsinyii ni. Bi o ti n wo ilu bo taara niyi, e yara lo ba a. Awon eniyan ni ebo kan ti won oo ru ni ori oke lonii.
Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run,ìrìn Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ rẹ̀.
Won ti ri irin re, Olorun,irin Olorun mi ati oba mi ni ibi mimo re.
“ Ọ̀nà kan wà tí ó dúró ṣánṣán lójú ènìyàn , ṣùgbọ́n àwọn ọ̀nà ikú ni òpin rẹ̀ ní àsẹ̀yìnwá - àsẹ̀yìnbọ̀ . ” ​ — Òwe 14 : 12 .
" Ona kan wa ti o duro sansan loju eniyan , sugbon awon ona iku ni opin re ni aseyinwa - aseyinbo . " -- Owe 14 : 12 .
Wọ́n á tipa bẹ́ẹ̀ di ọmọlẹ́yìn Jésù tí Ọlọ́run ti sọ dọmọ .
Won a tipa bee di omoleyin Jesu ti Olorun ti so domo .
ikonioni
ikonioni
Kì í ṣe pé gbogbo èrò inú wọn burú , àmọ́ ó gba àkókò àti ìsapá kí ọkàn èèyàn tó lè di èyí tó ń múnú Jèhófà Ọlọ́run dùn ní ti gidi .
Ki i se pe gbogbo ero inu won buru , amo o gba akoko ati isapa ki okan eeyan to le di eyi to n munu Jehofa Olorun dun ni ti gidi .
Ara Ísírẹ́lì tẹ̀mí làwọn àpọ́sítélì tí Jésù ń bá sọ̀rọ̀ wà , wọn kì í ṣe onídàájọ́ àwọn arákùnrin wọn .
Ara Isireli temi lawon apositeli ti Jesu n ba soro wa , won ki i se onidaajo awon arakunrin won .
Jèhófà ni Orísun òtítọ́ tẹ̀mí .
Jehofa ni Orisun otito temi .
Kí ló ń lé wọn láré ná ?
Ki lo n le won lare na ?
ǸJẸ́ ó ti ṣòro fún ẹ rí láti lóye ọ̀nà tí àwọn ẹlòmíì ń gbà ronú ?
NJE o ti soro fun e ri lati loye ona ti awon elomii n gba ronu ?
Ó pàdé abaraméjì kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Mike (Sambasa Nzeribe), ẹnití ó nílò ìrànlọ́wọ́ ọmọbìrin náà láti bá àwọn ènìyan tí ó fi sílẹ̀ sọ̀rọ̀.
O pade abarameji kan ti oruko re n je Mike (Sambasa Nzeribe), eniti o nilo iranlowo omobirin naa lati ba awon eniyan ti o fi sile soro.
Torí a jẹ́ aláìpé , a máa ń ṣe ohun tó lè bí àwọn míì nínú nígbà míì , àwọn náà sì lè ṣe bẹ́ẹ̀ sí wa .
Tori a je alaipe , a maa n se ohun to le bi awon mii ninu nigba mii , awon naa si le se bee si wa .
49, Ní ọjọ náà, a o wọ wọn nínú
49, Ni ojo naa, a o wo won ninu
Àbẹ̀wò tó ṣe sí ibẹ̀ sì kẹ́sẹ járí gan - an ni , bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn àlùfáà gbìyànjú láti da ìpàdé náà rú nípa fífariwobọnu àti nípa wíwó àwọn àga mọ́lẹ̀ .
Abewo to se si ibe si kese jari gan - an ni , bo tile je pe awon alufaa gbiyanju lati da ipade naa ru nipa fifariwobonu ati nipa wiwo awon aga mole .
Kí ni yóò mú irú ìyípadà bẹ́ẹ̀ wá ?
Ki ni yoo mu iru iyipada bee wa ?
Tí wọ́n bá sọ ohun tó ń jẹ wọ́n lọ́kàn fún ẹ , má ṣe ronú pé àsìkò ti wọn ti kọjá lọ .
Ti won ba so ohun to n je won lokan fun e , ma se ronu pe asiko ti won ti koja lo .