diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Láti ọdún mẹ́ta sẹ́yìn , àwọn Ẹlẹ́rìí tí iye wọn jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ó lé ọgọ́rùn - ún méje àti mọ́kànlá [ 3,711 ] ló ti jàǹfààní látinú àwọn ètò ìdálẹ́kọ̀ọ́ náà .
Lati odun meta seyin , awon Elerii ti iye won je egberun meta o le ogorun - un meje ati mokanla [ 3,711 ] lo ti janfaani latinu awon eto idalekoo naa .
oṣú keje ọdún yi tun
osu keje odun yi tun
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 23 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 23 ]
Kí arakunrin tí ó jẹ́ mẹ̀kúnnù kí ó yọ̀ nígbà tí Ọlọrun bá gbé e ga.
Ki arakunrin ti o je mekunnu ki o yo nigba ti Olorun ba gbe e ga.
Ìran tí a fi hàn mí yìí le:Àwọn oníjàgídíjàgan lọ digun kó ìkógun,abanǹkanjẹ́ sì ba nǹkan jẹ́.Ẹ̀yin ará Elamu, ẹ gòkè lọ!Ẹ̀yin ará Media, ẹ múra ogun!Mo ti fòpin sí òṣé ati ìjìyà tí Babiloni kó bá gbogbo eniyan.
Iran ti a fi han mi yii le:Awon onijagidijagan lo digun ko ikogun,abannkanje si ba nnkan je.Eyin ara Elamu, e goke lo!Eyin ara Media, e mura ogun!Mo ti fopin si ose ati ijiya ti Babiloni ko ba gbogbo eniyan.
O fi ayé gúnlẹ̀ lórí àwọn ìpìlẹ̀;tí a kò le è mì láéláé.
O fi aye gunle lori awon ipile;ti a ko le e mi laelae.
Ọṣẹ́ wo gan - an ni ọ̀tẹ̀ náà ti ṣe fún ẹ̀dá ènìyàn ?
Ose wo gan - an ni ote naa ti se fun eda eniyan ?
Ṣé o sì ń ya ara rẹ sọ́tọ̀ nínú ayé yìí ? — Ka 2 Pétérù 3 : 11 , 12 .
Se o si n ya ara re soto ninu aye yii ? — Ka 2 Peteru 3 : 11 , 12 .
Ẹ jọ máa ṣe àwọn ohun tẹ́ ẹ máa ń ṣe nígbà tẹ́ ẹ ṣì ń fẹ́ra yín sọ́nà tàbí nígbà tẹ́ ẹ ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣègbéyàwó .
E jo maa se awon ohun te e maa n se nigba te e si n fera yin sona tabi nigba te e sese segbeyawo .
Ǹjẹ́ kí ìṣarasíhùwà rẹ dà bíi ti Dáfídì tó kọrin pé : “ Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà , àní ọ̀dọ̀ rẹ ni àwọn ènìyàn ẹlẹ́ran ara gbogbo yóò wá .
Nje ki isarasihuwa re da bii ti Dafidi to korin pe : “ Iwo Olugbo adura , ani odo re ni awon eniyan eleran ara gbogbo yoo wa .
Ọrúnmìlà ni ìgbà tôo bá gẹgùn tán
Orunmila ni igba too ba gegun tan
“ Ó dá mi lójú gbangba pé mi ò ṣàṣìṣe rárá lọ́dún márùn - ún sẹ́yìn ( nígbà tí mo wà ní Etíkun Moresby ) fún kíkà tí mo ka ìwé ìròyìn Jí !
" O da mi loju gbangba pe mi o sasise rara lodun marun - un seyin ( nigba ti mo wa ni Etikun Moresby ) fun kika ti mo ka iwe iroyin Ji !
inú ire
inu ire
Kò sí ẹni tí yóo gba ẹjọ́ yín rò,kò ní sí òògùn fún ọgbẹ́ yín,kò ní sí ìwòsàn fun yín.
Ko si eni ti yoo gba ejo yin ro,ko ni si oogun fun ogbe yin,ko ni si iwosan fun yin.
Àwọn tí mo fọwọ́ mi dá fún ara mi,kí wọ́n lè kéde ògo mi.
Awon ti mo fowo mi da fun ara mi,ki won le kede ogo mi.
Ó sọ pé : “ Ẹ sá fún ìbọ̀rìṣà . ”
O so pe : " E sa fun iborisa . "
Nítorí pé Ọlọ́run yín aláàánú ni, kò ní gbàgbé tàbí pa yín rẹ́ tàbí kó gbàgbé májẹ̀mú pẹ̀lú àwọn baba ńlá yín, èyí tí ó fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ nípa ìbúra.
Nitori pe Olorun yin alaaanu ni, ko ni gbagbe tabi pa yin re tabi ko gbagbe majemu pelu awon baba nla yin, eyi ti o fi idi re mule nipa ibura.
sọfún un (ìyàwò), òun (ìyàwô) wí
sofun un (iyawo), oun (iyawo) wi
10 : 29 — Kí ni “ ọ̀nà Jèhófà ” ?
10 : 29 -- Ki ni " ona Jehofa " ?
Ó tún tẹnu mọ́ ọn pé “ orúkọ Baba [ òun ] ” ni òun fi ń ṣe àwọn iṣẹ́ tóun ń ṣe .
O tun tenu mo on pe " oruko Baba [ oun ] " ni oun fi n se awon ise toun n se .
▪ Ìgbésí Ayé Yìí Ha Ni Gbogbo Ohun Tí Ó Wà Bí ?
# Igbesi Aye Yii Ha Ni Gbogbo Ohun Ti O Wa Bi ?
Olódodo ṣègbékò sí ẹnìkan tí ó rò ó lọ́kàn ara rẹ̀;a mú àwọn ẹni mímọ́ lọ,kò sì ṣí ẹni tó yépé a ti mú àwọn olódodo lọláti yọ wọ́n kúrò nínú ibi.
Olododo segbeko si enikan ti o ro o lokan ara re;a mu awon eni mimo lo,ko si si eni to yepe a ti mu awon olododo lolati yo won kuro ninu ibi.
Yàtọ̀ sí ìyẹn , àwọn alàgbà tó ní irú ẹ̀mí tí Jésù dámọ̀ràn rẹ̀ máa ń bọlá fún àwọn mẹ́ńbà yòókù nínú ìjọ , bí Jèhófà ṣe ń bọlá fún àwọn adúróṣinṣin olùjọsìn rẹ̀ àti bí Jésù Kristi ṣe ń bọlá fún àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ tó dúró ṣinṣin .
Yato si iyen , awon alagba to ni iru emi ti Jesu damoran re maa n bola fun awon menba yooku ninu ijo , bi Jehofa se n bola fun awon adurosinsin olujosin re ati bi Jesu Kristi se n bola fun awon omoleyin re to duro sinsin .
Bí ẹnikẹ́ni nínú yín bá ni èdè-àìyedè sí ẹnikejì rẹ̀, ó ha gbọdọ̀ lọ pè é lẹ́jọ́ níwájú àwọn aláìsòótọ́ bí, bí kò se níwájú àwọn ènìyàn mímọ́
Bi enikeni ninu yin ba ni ede-aiyede si enikeji re, o ha gbodo lo pe e lejo niwaju awon alaisooto bi, bi ko se niwaju awon eniyan mimo
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Mú Ìbànújẹ́ Kúrò Lọ́kàn Mi ?
Bawo Ni Mo Se Le Mu Ibanuje Kuro Lokan Mi ?
(ẹ̀dà mìíràn)
(eda miiran)
“ Ìwà ìkà tí wọ́n hù káàkiri orílẹ̀ - èdè náà kọjá àfẹnusọ . . . , ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn tí wọ́n pa láìṣe ẹjọ́ wọn tàbí láìṣe àkọsílẹ̀ iye tí wọ́n jẹ́ ; àwọn èèyàn tí wọ́n rán lọ sí ìgbèkùn àtàwọn àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ , àwọn èèyàn tí wọ́n fi ẹ̀tọ́ wọn dù nítorí iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe àti nítorí ìlú ìbílẹ̀ tí wọ́n ti wá . . . .
“ Iwa ika ti won hu kaakiri orile - ede naa koja afenuso . . . , oke aimoye eeyan ti won pa laise ejo won tabi laise akosile iye ti won je ; awon eeyan ti won ran lo si igbekun atawon ago iseninisee , awon eeyan ti won fi eto won du nitori ise ti won n se ati nitori ilu ibile ti won ti wa . . . .
Ní àfikún sí ìyẹn wọ́n tún dúró fún gbogbo àwọn alábòójútó nínú ìjọ . — 10 / 15 , ojú ìwé 14 .
Ni afikun si iyen won tun duro fun gbogbo awon alaboojuto ninu ijo . -- 10 / 15 , oju iwe 14 .
Torí pé mo máa ń jà gan - an , ọ̀pọ̀ ìgbà ló jẹ́ pé àgọ́ ọlọ́pàá ni mo ti máa ń lo òpin ọ̀sẹ̀ tàbí kó jẹ́ ilé ìwòsàn níbi tí wọ́n ti ń bá mi rán ojú ọgbẹ́ .
Tori pe mo maa n ja gan - an , opo igba lo je pe ago olopaa ni mo ti maa n lo opin ose tabi ko je ile iwosan nibi ti won ti n ba mi ran oju ogbe .
● Fúnni lẹ́bùn kí wọ́n sì máa láyọ̀ ni ?
* Funni lebun ki won si maa layo ni ?
Èyí sì bà mí lọ́kàn jẹ́ gidigidi .
Eyi si ba mi lokan je gidigidi .
Nítorí náà , nígbà tí Ọlọ́run sọ pé Jóòbù jẹ́ aláìlẹ́bi , òótọ́ ọ̀rọ̀ ni , ní ti pé ó ṣe gbogbo ohun tí Ọlọ́run retí lọ́dọ̀ ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó jẹ́ ẹ̀dá ènìyàn aláìpé àti ẹlẹ́ṣẹ̀ .
Nitori naa , nigba ti Olorun so pe Joobu je alailebi , ooto oro ni , ni ti pe o se gbogbo ohun ti Olorun reti lodo okan lara awon iranse re to je eda eniyan alaipe ati elese .
Tó o bá ń fẹ́ ìsọfúnni sí i nípa àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà , wo fídíò yìí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ​ — A Ṣètò Wa Láti Wàásù Ìhìn Rere , lórí ìkànnì www.jw.org / yo .
To o ba n fe isofunni si i nipa awa Elerii Jehofa , wo fidio yii Awa Elerii Jehofa ​ — A Seto Wa Lati Waasu Ihin Rere , lori ikanni www.jw.org / yo .
Ẹni tí ó tẹ̀lé e ninu àwọn ọ̀gágun olókìkí mẹta náà ni Eleasari ọmọ Dodo ará Aho.
Eni ti o tele e ninu awon ogagun olokiki meta naa ni Eleasari omo Dodo ara Aho.
Ọkàn tí ó bá ṣẹ̀ ní yóò kú. Ọmọ kò ní í ru ẹ̀bi baba rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni baba náà kò ní ru ẹ̀bi ọmọ rẹ̀. Ìwà rere ènìyàn rere yóò wà lórí rẹ̀, ìwà búburú ti ènìyàn búburú náà la ó kà sí i lọ́rùn.
Okan ti o ba se ni yoo ku. Omo ko ni i ru ebi baba re, bee ni baba naa ko ni ru ebi omo re. Iwa rere eniyan rere yoo wa lori re, iwa buburu ti eniyan buburu naa la o ka si i lorun.
Kò sì sẹ́nì kankan láti ibùgbé àwọn ẹni ẹ̀mí tó tíì ṣe wọ́n ní jàǹbá . ”
Ko si seni kankan lati ibugbe awon eni emi to tii se won ni janba . ”
Jèhófà rántí Sámúsìnì nípa fífún un ní agbára tó ju tí ẹ̀dá lọ , tó fi jẹ́ pé ó lè gbẹ̀san ara rẹ̀ lára àwọn ọ̀tá Ọlọ́run .
Jehofa ranti Samusini nipa fifun un ni agbara to ju ti eda lo , to fi je pe o le gbesan ara re lara awon ota Olorun .
Ó dá wa lójú pé ojúlówó àpẹẹrẹ nípa bí Ọlọ́run ṣe ṣèdájọ́ àwọn ẹni búburú ló lò .
O da wa loju pe ojulowo apeere nipa bi Olorun se sedajo awon eni buburu lo lo .
Nígbà tí ọmọ náà dàgbà, ó sì gbà á lẹ́nu ọmú, ní ọjọ́ tí a gba Isaaki lẹ́nu ọmú, Abrahamu ṣe àsè ńlá.
Nigba ti omo naa dagba, o si gba a lenu omu, ni ojo ti a gba Isaaki lenu omu, Abrahamu se ase nla.
ẹ̀mí wọn nígbà tí wọn n ṣe àbòsí
emi won nigba ti won n se abosi
Èmi dún gẹ́gẹ́ bí àkọ̀ tàbí alápáǹdẹ̀dẹ̀,Èmi káàánú gẹ́gẹ́ bí aṣọ̀fọ̀ àdàbà.Ojú mi rẹ̀wẹ̀sì gẹ́gẹ́ bí mo ti ń wo àwọn ọ̀run.Ìdààmú bá mi; Ìwọ , wá fún ìrànlọ́wọ́ mi!”
Emi dun gege bi ako tabi alapandede,Emi kaaanu gege bi asofo adaba.Oju mi rewesi gege bi mo ti n wo awon orun.Idaamu ba mi; Iwo , wa fun iranlowo mi!"
Ló bá sọ fún mi pé : “ Lọ́ sórí pèpéle kó o sì sọ ìtàn náà fún mi . ”
Lo ba so fun mi pe : “ Lo sori pepele ko o si so itan naa fun mi . ”
Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ Jésù nípa ìpọ́njú ńlá ṣe rí lára àwa èèyàn Jèhófà ?
Bawo ni asotele Jesu nipa iponju nla se ri lara awa eeyan Jehofa ?
Àwọn ẹranko , irúgbìn , àtàwọn kòkòrò pẹ̀lú ti fi ibi tí Ọlọ́run dá wọn sí sílẹ̀ wọ́n sì ti forí lé àwọn kọ́ńtínẹ́ǹtì mìíràn .
Awon eranko , irugbin , atawon kokoro pelu ti fi ibi ti Olorun da won si sile won si ti fori le awon kontinenti miiran .
Rírí ìdáhùn sí ìbéèrè yìí lè ṣèrànwọ́ láti mú ohun kejì tó ń fa ìwà ibi kúrò , ìyẹn àìní ìmọ̀ nípa ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe .
Riri idahun si ibeere yii le seranwo lati mu ohun keji to n fa iwa ibi kuro , iyen aini imo nipa ohun ti Olorun fe se .
Kí lèyí ṣàpèjúwe ?
Ki leyi sapejuwe ?
Wọ́n lóun ló ń fa ipò ojú ọjọ́ tí kò bára dé káàkiri ayé , irú bí ọ̀dá , òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá , ìgbì ooru gbígbóná àti ìjì líle .
Won loun lo n fa ipo oju ojo ti ko bara de kaakiri aye , iru bi oda , ojo arooroda , igbi ooru gbigbona ati iji lile .
Bí Bíbélì ti ṣèlérí , ọgbọ́n tó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá lè jẹ́ kí wọ́n mọ ọ̀nà tí wọ́n lè gbà dáàbò bò ara wọn nípa tẹ̀mí .
Bi Bibeli ti seleri , ogbon to ti odo Olorun wa le je ki won mo ona ti won le gba daabo bo ara won nipa temi .
Ó kọ àwọn orin tó lè jẹ́ kí èèyàn ronú jinlẹ̀ àtàwọn sáàmù tó sọ nípa iṣẹ́ olùṣọ́ àgùntàn agbo ẹran .
O ko awon orin to le je ki eeyan ronu jinle atawon saamu to so nipa ise oluso aguntan agbo eran .
Òpìtàn Jacques le Goff , tó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Faransé sọ pé : “ Nígbà tó fi máa di òpin ọ̀rúndún kẹtàlá , kò síbi tí ẹ̀kọ́ pọ́gátórì ò tíì dé . ”
Opitan Jacques le Goff , to je omo ile Faranse so pe : “ Nigba to fi maa di opin orundun ketala , ko sibi ti eko pogatori o tii de . ”
Ọ̀pọ̀ obìnrin ni irú nǹkan bẹ́ẹ̀ máa ń dùn , títí kan àwọn tó o rò pé àwọn ọkùnrin gba tiwọn gan - an !
Opo obinrin ni iru nnkan bee maa n dun , titi kan awon to o ro pe awon okunrin gba tiwon gan - an !
Ó dájú pé “ àwọn àsọjáde tí àwọn wòlíì mímọ́ ti sọ ní ìṣáájú ” ni Pọ́ọ̀lù àti Pétérù kọ sínú lẹ́tà wọn .
O daju pe “ awon asojade ti awon wolii mimo ti so ni isaaju ” ni Poolu ati Peteru ko sinu leta won .
àbá náà wọlé ìbéèrè yìí
aba naa wole ibeere yii
Ó sì wí fún wọn pé, Kì í ṣe ti yín ni láti mọ àkókò tàbí ìgbà tí Baba ti yàn nípa àṣẹ òun tìkárarẹ̀
O si wi fun won pe, Ki i se ti yin ni lati mo akoko tabi igba ti Baba ti yan nipa ase oun tikarare
Ẹwà Ìṣẹ̀dá Jèhófà
Ewa Iseda Jehofa
• Báwo la ṣe ń fi hàn pé a gbà pé Jésù ni Ṣílò náà , irú ẹ̀mí wo la sì gbọ́dọ̀ yẹra fún ?
• Bawo la se n fi han pe a gba pe Jesu ni Silo naa , iru emi wo la si gbodo yera fun ?
Ṣó o gbádùn kíka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lẹ́nu àìpẹ́ yìí ?
So o gbadun kika awon Ile Iso to jade lenu aipe yii ?
Ènìyàn kò mọ iye rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni a kò le è rí i ní ilẹ̀ àwọn alààyè.
Eniyan ko mo iye re,bee ni a ko le e ri i ni ile awon alaaye.
Lẹ́yìn náà Mose pa á, ó tọ́ ninu ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, ó fi kan etí ọ̀tún Aaroni, ati àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ati àtàǹpàkò ẹsẹ̀ ọ̀tún rẹ̀.
Leyin naa Mose pa a, o to ninu eje re, o fi kan eti otun Aaroni, ati atanpako owo otun re, ati atanpako ese otun re.
Nígbàtí Ámúlẹ́kì rí ìrora
Nigbati Amuleki ri irora
Kì í ṣe àwọn ọ̀dọ́ nìkan ni ò mọ ìpèníjà tó lè dé lọ́jọ́ iwájú .
Ki i se awon odo nikan ni o mo ipenija to le de lojo iwaju .
Mò ń bá ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì mi lọ fún nǹkan bí ọdún kan .
Mo n ba ikekoo Bibeli mi lo fun nnkan bi odun kan .
onígun
onigun
Bí ẹ̀kọ́ àwọn kèfèrí onímọ̀ ọgbọ́n orí ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í yọ́ wọnú ẹ̀kọ́ ìsìn àwọn Júù àti tàwọn oníṣọ́ọ̀ṣì nìyẹn , títí kan ẹ̀kọ́ pé ẹ̀mí èèyàn máa ń lọ síbì kan téèyàn bá kú .
Bi eko awon keferi onimo ogbon ori se bere si i yo wonu eko isin awon Juu ati tawon onisoosi niyen , titi kan eko pe emi eeyan maa n lo sibi kan teeyan ba ku .
Èdè Gẹ̀ẹ́sì làwọn olùkọ́ mi nílé ìwé ń sọ , òun làwọn ọ̀rẹ́ mi ń sọ , òun náà sì lèmi àtàwọn àbúrò mi máa ń sọ síra wa .
Ede Geesi lawon oluko mi nile iwe n so , oun lawon ore mi n so , oun naa si lemi atawon aburo mi maa n so sira wa .
Nasho Dori ní kí Arákùnrin Gole Flloko tó wà ní ìlú Gjirokastër ràn mí lọ́wọ́ .
Nasho Dori ni ki Arakunrin Gole Flloko to wa ni ilu Gjirokaster ran mi lowo .
Ó tún wí pé, “Ta ni ó lè sọ fún Abrahamu pé Sara yóo fún ọmọ lọ́mú? Sibẹsibẹ mo bí ọmọ fún un nígbà tí ó ti di arúgbó.”
O tun wi pe, "Ta ni o le so fun Abrahamu pe Sara yoo fun omo lomu? Sibesibe mo bi omo fun un nigba ti o ti di arugbo."
Pọ́ọ̀lù tún sọ kókó kan náà yìí nígbà tó rọ àwọn Kristẹni ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ ní Kólósè pé kí wọ́n “ máa rìn lọ́nà tí ó yẹ Jèhófà fún ète wíwù ú ní kíkún ” nípa “ síso èso nínú iṣẹ́ rere gbogbo ” kí wọ́n sì máa “ pọ̀ sí i nínú ìmọ̀ pípéye nípa Ọlọ́run . ”
Poolu tun so koko kan naa yii nigba to ro awon Kristeni elegbe re ni Kolose pe ki won " maa rin lona ti o ye Jehofa fun ete wiwu u ni kikun " nipa " siso eso ninu ise rere gbogbo " ki won si maa " po si i ninu imo pipeye nipa Olorun . "
Ìwọ ní ẹ̀rù, Ọlọ́run, ní ibi mímọ́ Rẹ
Iwo ni eru, Olorun, ni ibi mimo Re
Yàtọ̀ síyẹn , Jòhánù nìkan ló sọ pé , “ Ọlọ́run jẹ́ ìfẹ́ . ”
Yato siyen , Johanu nikan lo so pe , " Olorun je ife . "
Mo rí i pé bí mo ṣe ń fowó ṣètìlẹ́yìn ti jẹ́ kí n túbọ̀ máa nífẹ̀ẹ́ àwọn èèyàn .
Mo ri i pe bi mo se n fowo setileyin ti je ki n tubo maa nifee awon eeyan .
Jakọbu bá dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, ó gbé òkúta tí ó fi ṣe ìrọ̀rí nàró gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ̀n, ó sì da òróró sórí rẹ̀.
Jakobu ba dide ni owuro kutukutu, o gbe okuta ti o fi se irori naro gege bi owon, o si da ororo sori re.
Báwo ni wọ́n ṣe ń di ẹrú ?
Bawo ni won se n di eru ?
Ijoba orile-ede Britain ni o se idawole yi nipa ki o le ijerisi ominira orile-ede Nigeria ni odun 1960.[2]
Ijoba orile-ede Britain ni o se idawole yi nipa ki o le ijerisi ominira orile-ede Nigeria ni odun 1960.[2]
Ó sì sọ pé “ kò sẹ́ni tó gbọ́dọ̀ mú ohunkóhun tàbí gba . . . ohunkóhun lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni , àyàfi tó bá gba ìwé àṣẹ lọ́dọ̀ mi . ”
O si so pe " ko seni to gbodo mu ohunkohun tabi gba . . . ohunkohun lowo enikeni , ayafi to ba gba iwe ase lodo mi . "
Wo “ Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé ” nínú Ilé Ìṣọ́ June 15 , 2004 , ojú ìwé 29 sí 31 .
Wo " Ibeere Lati Owo Awon Onkawe " ninu Ile Iso June 15 , 2004 , oju iwe 29 si 31 .
gígá
giga
Bí ẹ bá wòkè tí ẹ rí oòrùn, òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀: àwọn ohun tí a ṣe lọ́jọ̀ sójú ọ̀run, ẹ má ṣe jẹ́ kí wọ́n tàn yín jẹ dé bi pé ẹ̀yin yóò foríbalẹ̀ fún wọn, àti láti máa sin ohun tí Ọlọ́run yín dá fún gbogbo orílẹ̀-èdè lábẹ́ ọ̀run.
Bi e ba woke ti e ri oorun, osupa ati awon irawo: awon ohun ti a se lojo soju orun, e ma se je ki won tan yin je de bi pe eyin yoo foribale fun won, ati lati maa sin ohun ti Olorun yin da fun gbogbo orile-ede labe orun.
Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù tó fi hàn pé “ ẹ̀rí ìfọwọ́sọ̀yà ” wà pé Ọlọ́run á jí òkú dìde dájúdájú ló wọ̀ wọ́n lọ́kàn .
O see se ko je pe oro Poolu to fi han pe " eri ifowosoya " wa pe Olorun a ji oku dide dajudaju lo wo won lokan .
A ò tiẹ̀ fìgbà kan rò ó rí pé nígbà tá a bá lé ní ẹni ọgọ́ta ọdún la ó ṣẹ̀ṣẹ̀ wá máa kọ́ èdè kan tá ò mọ̀ tẹ́lẹ̀ ká bàa lè bá àwọn ará Ìpẹ̀kun Ìlà Oòrùn ayé sọ̀rọ̀ .
A o tie figba kan ro o ri pe nigba ta a ba le ni eni ogota odun la o sese wa maa ko ede kan ta o mo tele ka baa le ba awon ara Ipekun Ila Oorun aye soro .
9 : 11 .
9 : 11 .
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ àwọn èèyàn ló ń gun kẹ̀kẹ́ lójoojúmọ́ .
Araadota oke awon eeyan lo n gun keke lojoojumo .
Èmi mú yín wá sí ilẹ̀ àwọn ará Ámórì tí ó ń gbé ìlà-oòrùn Jọ́dánì
Emi mu yin wa si ile awon ara Amori ti o n gbe ila-oorun Jodani
( b ) Báwo lo ṣe lè mú kí àjọṣe rẹ pẹ̀lú Jèhófà túbọ̀ lágbára ?
( b ) Bawo lo se le mu ki ajose re pelu Jehofa tubo lagbara ?
Bó o bá bẹ̀rẹ̀ ìrìn rẹ láti ibi àbáwọlé apá òkè , kedere báyìí ni wàá máa wo Òpópónà Curete tó lọ já sí Ibi Ìkówèésí Celsus lọ́ọ̀ọ́kán .
Bo o ba bere irin re lati ibi abawole apa oke , kedere bayii ni waa maa wo Opopona Curete to lo ja si Ibi Ikoweesi Celsus loookan .
Ọlọ́run Ọlọ́gbọ́n Fúnni Ní Ọ̀pọ̀ Ìkìlọ̀
Olorun Ologbon Funni Ni Opo Ikilo
Wáìnì kíkan ni , kì í ṣe omi àjàrà tí kò kan .
Waini kikan ni , ki i se omi ajara ti ko kan .
Àwọn Kristẹni ọ̀dọ́ kan ti lọ ń yọjú wòwòkuwò nínú Íńtánẹ́ẹ̀tì , èyí sì ti kó wọn sí yọ́ọ́yọ́ọ́ .
Awon Kristeni odo kan ti lo n yoju wowokuwo ninu Intaneeti , eyi si ti ko won si yooyoo .
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ , Sámúẹ́lì mú ìwo òróró , ó sì fòróró yàn án láàárín àwọn arákùnrin rẹ̀ .
Bee gege , Samueli mu iwo ororo , o si fororo yan an laaarin awon arakunrin re .
Kàkà bẹ́ẹ̀ , ó rí “ Ọba àwọn ọba àti Olúwa àwọn olúwa , ” ìyẹn Ọba Ìjọba Ọlọ́run .
Kaka bee , o ri “ Oba awon oba ati Oluwa awon oluwa , ” iyen Oba Ijoba Olorun .
Àmọ́ , kí ló yẹ kó o ṣe láwọn ìgbà tó bá dà bíi pé àwọn alágbàtọ́ rẹ kò ṣe ohun tó o rò pé ó tọ̀nà ?
Amo , ki lo ye ko o se lawon igba to ba da bii pe awon alagbato re ko se ohun to o ro pe o tona ?
Ẹ jẹ́ ká lo àpèjúwe yìí ná : Ọ̀pọ̀ wa ló fẹ́ràn ká máa jẹ ìpápánu lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan , àmọ́ tó bá jẹ́ ìpápánu bíi bisikíìtì , súìtì tàbí kéèkì lẹnì kan kúndùn , ó máa ṣàkóbá fún ìlera rẹ̀ .
E je ka lo apejuwe yii na : Opo wa lo feran ka maa je ipapanu leekookan , amo to ba je ipapanu bii bisikiiti , suiti tabi keeki leni kan kundun , o maa sakoba fun ilera re .
Lẹ́yìn tí ọkọ mi kú , kò rọrùn fún mi láti máa dá ṣe àwọn nǹkan .
Leyin ti oko mi ku , ko rorun fun mi lati maa da se awon nnkan .
Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 4 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
Apileko fun Ikekoo 4 OJU IWE 20 si 24
ṣúárì
suari
Ìpàdé yìí ni èmi àti ọ̀dọ́ Ẹlẹ́rìí kan tó ń jẹ́ Stéphane ti mọra , ó sì mú mi bí ọ̀rẹ́ .
Ipade yii ni emi ati odo Elerii kan to n je Stephane ti mora , o si mu mi bi ore .
Gomina ipinle Eko nigba ti isele naa sele, Akinwunmi Ambode so pe ileewe alakobere n gbe ile naa lona ofin nitori pe ile naa ti wa ni oruko gege bi ile ibugbe.
Gomina ipinle Eko nigba ti isele naa sele, Akinwunmi Ambode so pe ileewe alakobere n gbe ile naa lona ofin nitori pe ile naa ti wa ni oruko gege bi ile ibugbe.
Nígbà tí Pọ́ọ̀lù ń fún àwọn ọkùnrin tó wà nínú ìjọ ní ìṣírí pé kí wọ́n sakun láti kúnjú ìwọ̀n fún gbígba àǹfààní iṣẹ́ ìsìn tó pọ̀ sí i , kì í ṣe pé ó ń gba ẹnikẹ́ni níyànjú láti máa wá ipò ọlá .
Nigba ti Poolu n fun awon okunrin to wa ninu ijo ni isiri pe ki won sakun lati kunju iwon fun gbigba anfaani ise isin to po si i , ki i se pe o n gba enikeni niyanju lati maa wa ipo ola .
ìjọsìn). fún wíwá ojúure. àti
ijosin). fun wiwa ojuure. ati
Jíjí Èèyàn Gbé — Ǹjẹ́ Ojútùú Kan Tiẹ̀ Wà ?
Jiji Eeyan Gbe -- Nje Ojutuu Kan Tie Wa ?