diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Bó bá ti ń sún mọ́ ibi tí eré náà máa parí sí , bẹ́ẹ̀ ni yóò túbọ̀ máa jára mọ́ ọn kó lè kẹ́sẹ járí .
Bo ba ti n sun mo ibi ti ere naa maa pari si , bee ni yoo tubo maa jara mo on ko le kese jari .
Kí ni díẹ̀ lára ohun tá a fi ń dá ìsìn tòótọ́ mọ̀ ?
Ki ni die lara ohun ta a fi n da isin tooto mo ?
Mósè mọ ibi tí agbára òun mọ , ó si fi ọgbọ́n tẹ́wọ́ gba ìmọ̀ràn náà .
Mose mo ibi ti agbara oun mo , o si fi ogbon tewo gba imoran naa .
Take , for example , the case of Lázaro .
Take , for example , the case of Lazaro .
Sì wí fún àwọn ará Ámónì pé, Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run tí ó wí pé
Si wi fun awon ara Amoni pe, E gbo oro Oluwa Olorun ti o wi pe
Fọ́tò nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda British Museum
Foto nipase iyonda British Museum
ìràwọ) ní ẹ̀run, A sì ṣe wọn lỌsỌỌ
irawo) ni erun, A si se won lOsOO
ìdájọ́
idajo
Olówó-ayé kò wí ju báyìí lọ, Olódùmarè sì gbọ láti ọ̀run alákeji, nítorí kò sí ènìyàn ksn tí ó da bi màlákà, bẹ́ẹ̀ ni kò si aláfẹ̀hìntì kan tí o da bi Ọlọ́run Ọba.
Olowo-aye ko wi ju bayii lo, Olodumare si gbo lati orun alakeji, nitori ko si eniyan ksn ti o da bi malaka, bee ni ko si alafehinti kan ti o da bi Olorun Oba.
Ẹ̀rín Músẹ́ — Á Ṣe Ẹ́ Láǹfààní !
Erin Muse — A Se E Lanfaani !
Ó sì ṣe tí Móróníhà bọ́ síwájú
O si se ti Moroniha bo siwaju
Kàkà bẹ́ẹ̀ , máa ṣọ́ra fáwọn ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ Sátánì kó o lè ní ìgboyà àti okun láti sa gbogbo ipá rẹ láti lè máa ṣe ohun tó dára .
Kaka bee , maa sora fawon ogbon ewe Satani ko o le ni igboya ati okun lati sa gbogbo ipa re lati le maa se ohun to dara .
Torí pé Tímótì fi àwọn ohun tó kọ́ sílò , ìyẹn mú kó tóótun láti gba àwọn àǹfààní iṣẹ́ ìsìn míì . ​ — 1 Kọ́r .
Tori pe Timoti fi awon ohun to ko silo , iyen mu ko tootun lati gba awon anfaani ise isin mii . ​ — 1 Kor .
Baba wa ọ̀run tún pèsè “ olùrànlọ́wọ́ , ” ìyẹn ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ fún wa .
Baba wa orun tun pese " oluranlowo , " iyen emi mimo re fun wa .
Àwọn ẹlẹ́sìn lóríṣiríṣi bẹ̀rẹ̀ sí ronú pé ó ṣeé ṣe kó jẹ́ àwọn ẹ̀mí búburú ló ṣiṣẹ́ yìí .
Awon elesin lorisirisi bere si ronu pe o see se ko je awon emi buburu lo sise yii .
13 , 14 . ( a ) Kí ni ohun tí Jésù ò jẹ́ kó gbàfiyèsí òun bó ṣe ń ṣiṣẹ́ tó wá ṣe láyé ?
13 , 14 . ( a ) Ki ni ohun ti Jesu o je ko gbafiyesi oun bo se n sise to wa se laye ?
Kí á lé akátá jìnnà ká tó bá adìẹ wí.
Ki a le akata jinna ka to ba adie wi.
Ẹ̀yin òbí ni Ọlọ́run gbé iṣẹ́ lé lọ́wọ́ láti kọ́ àwọn ọmọ yín , torí náà ẹ ṣe iṣẹ́ yín bí iṣẹ́ .
Eyin obi ni Olorun gbe ise le lowo lati ko awon omo yin , tori naa e se ise yin bi ise .
Ọ̀dọ́bìnrin kan tiẹ̀ wà níbẹ̀ táwọn ọkùnrin tó ń bá a sùn lé ní ọgọ́rùn - ún , ó wá ń ṣe fọ́ńté pé : “ Èmi ni mo nira mi , ohun tó bá sì wù mí ni mo lè fira mi ṣe . ”
Odobinrin kan tie wa nibe tawon okunrin to n ba a sun le ni ogorun - un , o wa n se fonte pe : “ Emi ni mo nira mi , ohun to ba si wu mi ni mo le fira mi se . ”
Tí tọkọtaya bá ń sọ ọ̀rọ̀ “ kíkorò onínú burúkú àti ìbínú àti ìrunú àti ìlọgun àti ọ̀rọ̀ èébú ” sí ara wọn , ààbò tẹ̀mí tó wà lórí ìgbéyàwó wọn kò ní lágbára mọ́ .
Ti tokotaya ba n so oro “ kikoro oninu buruku ati ibinu ati irunu ati ilogun ati oro eebu ” si ara won , aabo temi to wa lori igbeyawo won ko ni lagbara mo .
Ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA, Ẹlẹ́dàá yín wí,ẹni tí ó ṣẹ̀dá yín láti inú oyún,tí yóo sì ràn yín lọ́wọ́:Ẹ má bẹ̀rù ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, iranṣẹ mi,Jeṣuruni, ẹni tí mo yàn.
E gbo ohun ti OLUWA, Eledaa yin wi,eni ti o seda yin lati inu oyun,ti yoo si ran yin lowo:E ma beru eyin omo Jakobu, iranse mi,Jesuruni, eni ti mo yan.
Mo sì gbìyànjú láti máa fi àwọn nǹkan tí mò ń kọ́ dánra wò .
Mo si gbiyanju lati maa fi awon nnkan ti mo n ko danra wo .
Báwo la ṣe lè fọpẹ́ hàn , ká sì fi hàn pé a mọyì àwọn àgbà ọkùnrin — ìyẹn àwọn alàgbà , tàbí alábòójútó — nínú ìjọ ?
Bawo la se le fope han , ka si fi han pe a moyi awon agba okunrin — iyen awon alagba , tabi alaboojuto — ninu ijo ?
Tí a bá gbára lé e , tí a kò gbára lé ara wa , kò ní fi wá sílẹ̀ .
Ti a ba gbara le e , ti a ko gbara le ara wa , ko ni fi wa sile .
Wọ́n sọ pé lóòótọ́ ni iye yẹn kéré sí iye tí wọ́n ti fojú bù tẹ́lẹ̀ , “ àmọ́ iye yìí ṣì ga jù tá a bá ń sọ nípa àwọn èèyàn tí ń jìyà nítorí ipò òṣì . ”
Won so pe loooto ni iye yen kere si iye ti won ti foju bu tele , " amo iye yii si ga ju ta a ba n so nipa awon eeyan ti n jiya nitori ipo osi . "
Bóyá ìjà kọnfú tó ń jà ló jẹ́ kó wá já fáfá , torí kì í fẹ́ gba ohunkóhun gbọ́ àyàfi téèyàn bá fi Ìwé Mímọ́ kan ti àlàyé rẹ̀ lẹ́yìn .
Boya ija konfu to n ja lo je ko wa ja fafa , tori ki i fe gba ohunkohun gbo ayafi teeyan ba fi Iwe Mimo kan ti alaye re leyin .
O lè máa fòyà torí pé o fẹ́ di ìránṣẹ́ Ọlọ́run , tó ní láti máa pa àwọn òfin rẹ̀ mọ́ , tó sì ní láti máa sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Ọlọ́run .
O le maa foya tori pe o fe di iranse Olorun , to ni lati maa pa awon ofin re mo , to si ni lati maa soro nipa oruko Olorun .
“Ègún ni fún ọ ní ààrin ìlú, ègún ni fún ọ ní oko.
"Egun ni fun o ni aarin ilu, egun ni fun o ni oko.
Ní ọjọ́ kẹrin, wọ́n péjọ ní àfonífojì Beraka. Ibẹ̀ ni wọ́n ti yin OLUWA. Nítorí náà ni wọ́n ṣe bẹ̀rẹ̀ sí pe ibẹ̀ ní Beraka títí di òní olónìí.
Ni ojo kerin, won pejo ni afonifoji Beraka. Ibe ni won ti yin OLUWA. Nitori naa ni won se bere si pe ibe ni Beraka titi di oni olonii.
OLUWA sọ fún Jehoiakini ọba, ọmọ Jehoiakimu, ọba Juda, pé, “Mo fi ara mi búra, èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Bí ó bá tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ ni òrùka èdìdì ọwọ́ ọ̀tún mi,
OLUWA so fun Jehoiakini oba, omo Jehoiakimu, oba Juda, pe, "Mo fi ara mi bura, emi OLUWA ni mo so bee. Bi o ba tile je pe iwo ni oruka edidi owo otun mi,
Jésù Kristi lẹni náà , tó wà ní ipò gíga lókè ọ̀run .
Jesu Kristi leni naa , to wa ni ipo giga loke orun .
Ipò òkú tí ọ̀pọ̀ jù lọ aráyé tó ti kú wà lọ̀rọ̀ Hébérù náà , Ṣìọ́ọ̀lù dúró fún .
Ipo oku ti opo ju lo araye to ti ku wa loro Heberu naa , Sioolu duro fun .
Ìwọra ṣàǹfààní . ”
Iwora sanfaani . ”
wọn... Olúwa rẹ kò sì ṣàì mọ
won... Oluwa re ko si sai mo
Lákòókò tí Jeremáyà wà láyé , àwọn ará ilẹ̀ Lìdíà , bẹ̀rẹ̀ sí í lo ohun kan tó mú kí òwò ṣíṣe rọrùn , ìyẹn owó ẹyọ tí wọ́n fi òǹtẹ̀ ìjọba lù , tó sì ní ìwọ̀n bó ṣe yẹ kó wúwo tó .
Lakooko ti Jeremaya wa laye , awon ara ile Lidia , bere si i lo ohun kan to mu ki owo sise rorun , iyen owo eyo ti won fi onte ijoba lu , to si ni iwon bo se ye ko wuwo to .
Gbogbo èèyàn ló sì ní wọn lọ́wọ́ .
Gbogbo eeyan lo si ni won lowo .
òmíràn ìta-ẹ̀jẹ̀-sílẹ̀ yíò wà, àti ìbẹ̀wò nlá lãrín wọn; nítorí-èyi, ẹ̀yin ọmọkùnrin mi, èmi fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó rántí; bẹ̃ni, èmi fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó fetísílẹ̀ sí àwọn ọ̀rọ̀ mi.
omiran ita-eje-sile yio wa, ati ibewo nla larin won; nitori-eyi, eyin omokunrin mi, emi fe ki eyin ki o ranti; beni, emi fe ki eyin ki o fetisile si awon oro mi.
Àmọ́ , kí la lè ṣe táá mú ká túbọ̀ máa ṣèpinnu tó tọ́ ?
Amo , ki la le se taa mu ka tubo maa sepinnu to to ?
Ìròyìn kan sọ pé : “ Àwọn ará ṣètò ìrànlọ́wọ́ láti dín ìṣòro kù ní gbogbo àgbègbè El Salvador .
Iroyin kan so pe : “ Awon ara seto iranlowo lati din isoro ku ni gbogbo agbegbe El Salvador .
Kí ni tọkọtaya lè máa ṣe táá fi hàn pé wọ́n jẹ́ kí Jèhófà wà nínú ìgbéyàwó wọn ?
Ki ni tokotaya le maa se taa fi han pe won je ki Jehofa wa ninu igbeyawo won ?
Bí àpẹẹrẹ , níbi ìgbéyàwó tó wáyé ní Kánà , ẹ̀rí wà pé ńṣe ni Màríà ń forí ṣe fọrùn ṣe níbi ìnáwó náà , àmọ́ àkọsílẹ̀ náà ò sọ̀rọ̀ nípa Jósẹ́fù rárá .
Bi apeere , nibi igbeyawo to waye ni Kana , eri wa pe nse ni Maria n fori se forun se nibi inawo naa , amo akosile naa o soro nipa Josefu rara .
Rákélì sì wí pé, Ọlọ́run ti ṣe ìdájọ́ mi
Rakeli si wi pe, Olorun ti se idajo mi
Nígbà kí ìgbà tí bá gbé onídàájọ́ dìde fún wọn, máa ń wà pẹ̀lú onídàájọ́ náà, a sì gbà wọ́n kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn ní ìwọ̀n ìgbà tí onídàájọ́ náà bá wà láààyè nítorí àánú wà ní ara wọn, nígbà tí wọ́n bá ké ìrora lábẹ́ àwọn tí ń tẹrí wọn ba, tí sì ń fi ìyà jẹ wọ́n.
Nigba ki igba ti ba gbe onidaajo dide fun won, maa n wa pelu onidaajo naa, a si gba won kuro ni owo awon ota won ni iwon igba ti onidaajo naa ba wa laaaye nitori aanu wa ni ara won, nigba ti won ba ke irora labe awon ti n teri won ba, ti si n fi iya je won.
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹni pípé ni Jésù , síbẹ̀ ó kọ́ onírúurú ẹ̀kọ́ nípa ìgbọràn .
Bo tile je pe eni pipe ni Jesu , sibe o ko oniruuru eko nipa igboran .
Ó sọ pé : “ Mo kẹ́kọ̀ọ́ pé ńṣe ni ká gba àwọn àṣìṣe wa kí a sì máa bá a lọ ní wíwá inú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún ìlàlóye sí i . ”
O so pe : “ Mo kekoo pe nse ni ka gba awon asise wa ki a si maa ba a lo ni wiwa inu Oro Olorun fun ilaloye si i . ”
Onísìn Kátólíìkì paraku làwọn òbí mi , nígbà tí mo wà ní kékeré , mo di ọmọ ìdí pẹpẹ .
Onisin Katoliiki paraku lawon obi mi , nigba ti mo wa ni kekere , mo di omo idi pepe .
Jésù sọ pé : “ Wò ó !
Jesu so pe : " Wo o !
àpósítélì
apositeli
Nípa bẹ́ẹ̀ , à ń fi ìháragàgà retí ìmúṣẹ apá tó ṣàrà ọ̀tọ̀ nínú àsọtẹ́lẹ̀ Ìsíkíẹ́lì yìí , ọkàn wa sì balẹ̀ pé “ Jèhófà mọ bí a ti ń dá àwọn ènìyàn tí ń fọkàn sin Ọlọ́run nídè kúrò nínú àdánwò . ”
Nipa bee , a n fi iharagaga reti imuse apa to sara oto ninu asotele Isikieli yii , okan wa si bale pe " Jehofa mo bi a ti n da awon eniyan ti n fokan sin Olorun nide kuro ninu adanwo . "
1 : 8 .
1 : 8 .
Nígbà tí gbogbo àwọn eniyan náà rékọjá sí òdìkejì odò Jọdani tán, OLUWA wí fún Joṣua pé,
Nigba ti gbogbo awon eniyan naa rekoja si odikeji odo Jodani tan, OLUWA wi fun Josua pe,
Àwọn ère mẹ́rin kan wà ní gbàgede rẹ̀ tó jojú ní gbèsè .
Awon ere merin kan wa ni gbagede re to joju ni gbese .
Èéṣe tí o fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mí?Èéṣe tí ó fi ń ru sókè nínú mi?Fi ìrètí rẹ sínú Ọlọ́run,nítorí èmi yóò máa yìn ín, Òun niOlùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.
Eese ti o fi n rewesi, iwo okan mi?Eese ti o fi n ru soke ninu mi?Fi ireti re sinu Olorun,nitori emi yoo maa yin in, Oun niOlugbala mi ati Olorun mi.
Saulu bèèrè pé, “Ta ni ọ́, Oluwa?”Ẹni náà bá dáhùn pé, “Èmi ni Jesu, ẹni tí ò ń ṣe inúnibíni sí.
Saulu beere pe, “Ta ni o, Oluwa?”Eni naa ba dahun pe, “Emi ni Jesu, eni ti o n se inunibini si.
8 Kò Ní Sí Àjálù Mọ́ !
8 Ko Ni Si Ajalu Mo !
Pétérù ṣàlàyé rẹ̀ lọ́nà yìí , ó ní : “ Fún ìdí yìí , ẹ̀yin ará , ẹ túbọ̀ máa sa gbogbo ipá yín láti mú pípè àti yíyàn yín dájú fún ara yín ; nítorí bí ẹ bá ń bá a nìṣó ní ṣíṣe nǹkan wọ̀nyí , ẹ kì yóò kùnà lọ́nàkọnà láé .
Peteru salaye re lona yii , o ni : “ Fun idi yii , eyin ara , e tubo maa sa gbogbo ipa yin lati mu pipe ati yiyan yin daju fun ara yin ; nitori bi e ba n ba a niso ni sise nnkan wonyi , e ki yoo kuna lonakona lae .
Níwọ̀n bí Jésù ti jẹ́ ẹni pípé , ketekete ni àléébù àwọn aláìpé ì bá máa hàn sí i .
Niwon bi Jesu ti je eni pipe , ketekete ni aleebu awon alaipe i ba maa han si i .
Ìyá Lémúẹ́lì rán an létí ọ̀pọ̀ lára àwọn ojúṣe wọ̀nyí .
Iya Lemueli ran an leti opo lara awon ojuse wonyi .
Lẹ́yìn tí orílẹ̀ - èdè náà ti rìn gba ibi Òkè Sínáì kọjá , wọ́n gúnlẹ̀ sí Réfídímù .
Leyin ti orile - ede naa ti rin gba ibi Oke Sinai koja , won gunle si Refidimu .
ìpele-ìpele, ìwọ yòò sì rí ÒJÒ tí yòò
ipele-ipele, iwo yoo si ri OJO ti yoo
Ẹ̀yìn ìyẹn ló wá kẹ́kọ̀ọ́ pé Ọlọ́run yóò fìdí ìdájọ́ òdodo múlẹ̀ fún gbogbo èèyàn lórí ilẹ̀ ayé kan tí a fọ̀ mọ́ tónítóní , níbi tí àwọn èèyàn onígbọràn ti lè gbádùn àlàáfíà àti ayọ̀ ayérayé .
Eyin iyen lo wa kekoo pe Olorun yoo fidi idajo ododo mule fun gbogbo eeyan lori ile aye kan ti a fo mo tonitoni , nibi ti awon eeyan onigboran ti le gbadun alaafia ati ayo ayeraye .
Bíi ti Jèhófà , ó yẹ kí àwa náà máa ní sùúrù .
Bii ti Jehofa , o ye ki awa naa maa ni suuru .
Àwọn kérúbù náà wà ní ipò gíga , iṣẹ́ pàtàkì ni wọ́n ń ṣe , iṣẹ́ wọn sì kan ipò tí Ọlọ́run wà gẹ́gẹ́ bí Ẹni Gíga Jù Lọ .
Awon kerubu naa wa ni ipo giga , ise pataki ni won n se , ise won si kan ipo ti Olorun wa gege bi Eni Giga Ju Lo .
Nǹkan wọ̀nyí ni mo kọ̀wé sí yín ní ti àwọn tí wọ́n fẹ́ ẹ mún un yín ṣìnà.
Nnkan wonyi ni mo kowe si yin ni ti awon ti won fe e mun un yin sina.
Síbẹ̀ , mo ń ṣe gbogbo ohun tí mo lè ṣe , mo sì nírètí pé ara mi á ṣì le sí i .
Sibe , mo n se gbogbo ohun ti mo le se , mo si nireti pe ara mi a si le si i .
Kí ló lè mú kí Ọlọ́run tẹ́wọ́ gba ẹbọ kan tàbí kó máà tẹ́wọ́ gbà á ?
Ki lo le mu ki Olorun tewo gba ebo kan tabi ko maa tewo gba a ?
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà gbà pé Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run ní ọdún 1914 àti pé , àwọn ọjọ́ ìkẹyìn bẹ̀rẹ̀ ní ọdún yẹn .
Awa Elerii Jehofa gba pe Jesu bere si i sakoso gege bi Oba Ijoba Olorun ni odun 1914 ati pe , awon ojo ikeyin bere ni odun yen .
Ó ní : “ Nígbà tí ẹ bá rí tí àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ogun adótini bá yí Jerúsálẹ́mù ká , nígbà náà ni kí ẹ mọ̀ pé ìsọdahoro rẹ̀ ti sún mọ́lé . ”
O ni : " Nigba ti e ba ri ti awon egbe omo ogun adotini ba yi Jerusalemu ka , nigba naa ni ki e mo pe isodahoro re ti sun mole . "
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 13 ]
kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ si wọ igbó lọ titi ó fi ṣi ọ̀nà dé ilẹ̀ àwọn Ará-Ọ̀run – àwọn ti wọn ńpè ni Abàmi-ẹ̀dá
kerekere o bere si wo igbo lo titi o fi si ona de ile awon Ara-Orun – awon ti won npe ni Abami-eda
Ọjọ́ díẹ̀ lẹ́yìn náà , mo gbọ́ tí àjèjì kan ń bá ọmọ ẹ̀gbọ́n bàbá mi sọ̀rọ̀ .
Ojo die leyin naa , mo gbo ti ajeji kan n ba omo egbon baba mi soro .
Láwọn apá ibì kan láyé sì rèé , àṣà ìṣẹ̀dálẹ̀ wọn ò fàyè gba kí ìdílé jọ máa jẹun pọ̀ tàbí kí wọ́n tiẹ̀ máa sọ̀rọ̀ nídìí oúnjẹ .
Lawon apa ibi kan laye si ree , asa isedale won o faye gba ki idile jo maa jeun po tabi ki won tie maa soro nidii ounje .
Àmọ́ bó ti wù kí ẹ̀dá èèyàn gbìyànjú tó , wọn ò lè ṣe é kó dà bí èyí tí Ọlọ́run dá gan - gan .
Amo bo ti wu ki eda eeyan gbiyanju to , won o le se e ko da bi eyi ti Olorun da gan - gan .
alagbigba. Irántí yín kéré púpọ.
alagbigba. Iranti yin kere pupo.
Bí mo tilẹ̀ ń rò pé mi ò yẹ lẹ́ni tó lè rojú rere rẹ̀ , ó kíyè sí mi , ó sì fi ìfẹ́ àti sùúrù bójú tó mi .
Bi mo tile n ro pe mi o ye leni to le roju rere re , o kiye si mi , o si fi ife ati suuru boju to mi .
Inú rẹ̀ ń dùn bó ṣe ń wo àwọn oko tó kún fún pòròpórò tí wọ́n ti gé ọkà rẹ̀ kúrò , èyí jẹ́ ẹ̀rí pé wọ́n ti ṣiṣẹ́ àṣekára fún ọ̀pọ̀ ọjọ́ .
Inu re n dun bo se n wo awon oko to kun fun poroporo ti won ti ge oka re kuro , eyi je eri pe won ti sise asekara fun opo ojo .
belṣsasari
belssasari
Mo relé ọkọ ní ọmọ ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún , Emmas Mzanga sì ni ọkọ mi .
Mo rele oko ni omo odun meeedogun , Emmas Mzanga si ni oko mi .
Àwọn ẹ̀yà Reubẹni ati ẹ̀yà Gadi bá pe pẹpẹ tí wọ́n tẹ́ ní, “Ẹ̀rí” nítorí wọ́n ní, “Pẹpẹ náà ni ẹ̀rí láàrin wa pé, OLUWA ni Ọlọrun.”
Awon eya Reubeni ati eya Gadi ba pe pepe ti won te ni, "Eri" nitori won ni, "Pepe naa ni eri laarin wa pe, OLUWA ni Olorun."
OKUN MẸDITARÉNÍÀ
OKUN MEDITARENIA
Ta ló lè mú ohun mímọ́ jádeláti inú ohun tí kò mọ́?Kò sí ẹni náà.
Ta lo le mu ohun mimo jadelati inu ohun ti ko mo?Ko si eni naa.
Tá a bá fẹ́ là á já , a ní láti fi gbogbo ọkàn wa sin Jèhófà Ọlọ́run , ká sì kẹ́kọ̀ọ́ ká lè mọ àwọn ìwà àti ìṣe tó máa dùn mọ́ ọn nínú .
Ta a ba fe la a ja , a ni lati fi gbogbo okan wa sin Jehofa Olorun , ka si kekoo ka le mo awon iwa ati ise to maa dun mo on ninu .
Yàtọ̀ síyẹn , ọkọ kan lè sọ fún ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí pé kò gbọ́dọ̀ kọ́ àwọn ọmọ òun lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ .
Yato siyen , oko kan le so fun iyawo re to je Elerii pe ko gbodo ko awon omo oun lekoo otito .
Ìran nípa Ọ̀pá Fìtílà.
Iran nipa Opa Fitila.
Wọ́n ní dáadáa díẹ̀ , àmọ́ wọ́n tún fi hàn pé ọgbọ́n kù fún ọmọ aráyé , ọ̀pọ̀ ìgbà sì ni ojúkòkòrò wọn ń fara hàn .
Won ni daadaa die , amo won tun fi han pe ogbon ku fun omo araye , opo igba si ni ojukokoro won n fara han .
méḿfísì
memfisi
Gba àdúrà pé kí Olúwa mú ejò náà kúrò lọ́dọ̀ wa
Gba adura pe ki Oluwa mu ejo naa kuro lodo wa
( Ka Númérì 16 : 5 . )
( Ka Numeri 16 : 5 . )
Kí ló fà á tí ọ̀dọ́bìnrin yìí fi ṣe irú ìyípadà ńlá bẹ́ẹ̀ ?
Ki lo fa a ti odobinrin yii fi se iru iyipada nla bee ?
Kí nìdí tá a fi nílò ìṣọ́ra nínú ìjọ lónìí ?
Ki nidi ta a fi nilo isora ninu ijo lonii ?
Ṣùgbọ́n ọjọ́ ń bọ̀, ni Olúwa wí, nígbà tí n ó rán àwọn tí ó da ọtí láti inú àwọn ìgò tí wọ́n ó sì dà á síta
Sugbon ojo n bo, ni Oluwa wi, nigba ti n o ran awon ti o da oti lati inu awon igo ti won o si da a sita
“Nígbà tí màlúù bá bímọ, tí àgùntàn bímọ, tí ewúrẹ́ sì bímọ, ọmọ náà gbọdọ̀ wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀ fún ọjọ́ méje. Láti ọjọ́ kẹjọ ni ó ti di ìtẹ́wọ́gbà fún ọrẹ àfinásun sí .
“Nigba ti maluu ba bimo, ti aguntan bimo, ti ewure si bimo, omo naa gbodo wa pelu iya re fun ojo meje. Lati ojo kejo ni o ti di itewogba fun ore afinasun si .
Àwọn wo ni “ àwọn ohun tí ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé , ” ọ̀nà wo sì ni wọ́n ń gbà dẹni tí Jèhófà kà sí olódodo ?
Awon wo ni " awon ohun ti n be lori ile aye , " ona wo si ni won n gba deni ti Jehofa ka si olododo ?
Ká sòótọ́ , gbogbo wa pátá là ń fẹ́ káwọn èèyàn mú un dá wa lójú pé àwọ́n mọyì wa àti pé a wúlò .
Ka sooto , gbogbo wa pata la n fe kawon eeyan mu un da wa loju pe awon moyi wa ati pe a wulo .
Ó mọ́gbọ́n dání pé ká fìmọrírì gba ìbáwí tẹ́nì kan kàn ṣàdéédéé fún wa .
O mogbon dani pe ka fimoriri gba ibawi teni kan kan sadeedee fun wa .
Títẹ́tí tí tọkọtaya àkọ́kọ́ tẹ́tí sí Èṣù , tí wọn ò kọ irọ́ tó pa mú kí wọ́n di apẹ̀yìndà .
Titeti ti tokotaya akoko teti si Esu , ti won o ko iro to pa mu ki won di apeyinda .
Bó bá sì jẹ́ pé ọmọ náà máa ń wọlé lákòókò , tó sì ṣeé fọkàn tán , ẹ dà á rò bóyá ẹ lè fi kún òmìnira rẹ̀ , kẹ́ ẹ sì máa jẹ́ kó pẹ́ díẹ̀ sí i lóde .
Bo ba si je pe omo naa maa n wole lakooko , to si see fokan tan , e da a ro boya e le fi kun ominira re , ke e si maa je ko pe die si i lode .
Epo lojú ọbẹ̀.
Epo loju obe.
ṣúbo
subo
O tún lè fún ẹnìkan níṣìírí tó o bá jíròrò ìtàn ìgbésí ayé ẹnìkan láti inú Bíbélì tí ohun tó ṣẹlẹ̀ sí i fara jọ ti onítọ̀hún .
O tun le fun enikan nisiiri to o ba jiroro itan igbesi aye enikan lati inu Bibeli ti ohun to sele si i fara jo ti onitohun .