diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Tún ronú nípa Sárà tó jẹ́ ìyá àgbà fún Jósẹ́fù . | Tun ronu nipa Sara to je iya agba fun Josefu . |
Mímọ̀ tá a mọ̀ pé àwọn áńgẹ́lì ń tì wá lẹ́yìn nínú iṣẹ́ ìwàásù náà ń múnú wa dùn gan - an | Mimo ta a mo pe awon angeli n ti wa leyin ninu ise iwaasu naa n munu wa dun gan - an |
A ò ní fẹ́ ṣe ohun tó máa múnú bí ẹni tá a bá fẹ́ràn . | A o ni fe se ohun to maa munu bi eni ta a ba feran . |
Seti náà sì bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Enoṣi.Láti àkókò náà lọ ni àwọn ènìyàn ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ké pe orúkọ . | Seti naa si bi omokunrin kan, o si pe oruko re ni Enosi.Lati akoko naa lo ni awon eniyan ti bere si ni ke pe oruko . |
ìyàn yóò wà láàrin rẹ | iyan yoo wa laarin re |
Ṣùgbọ́n , ìwé kan sọ pé , “ àjíǹde Jésù tó wáyé lọ́jọ́ Sunday tó tẹ̀ lé ọjọ́ tó kú làwọn ará Róòmù àtàwọn ará Alẹkisáńdíríà máa ń ṣe ìrántí rẹ̀ ní tiwọn , ” wọ́n wá pè é ní Àjíǹde Ìrékọjá . | Sugbon , iwe kan so pe , “ ajinde Jesu to waye lojo Sunday to te le ojo to ku lawon ara Roomu atawon ara Alekisandiria maa n se iranti re ni tiwon , ” won wa pe e ni Ajinde Irekoja . |
ìfìmọ̀sọ̀kan | ifimosokan |
Ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ yìí jẹ́ ká mọ ohun tí ojúlówó ìwà ọ̀làwọ́ jẹ́ . | Oro ti Jesu so yii je ka mo ohun ti ojulowo iwa olawo je . |
“ ‘Ẹnikẹ́ni tí a bá wẹ̀nù kúrò nínú ìsunjáde rẹ̀ gbọdọ̀ ka ọjọ́ méje fún àwọn ọjọ́ ìwẹ̀nùmọ́: kí ó fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì fi omi wẹ ara rẹ̀: yóò sì di mímọ́. | “ ‘Enikeni ti a ba wenu kuro ninu isunjade re gbodo ka ojo meje fun awon ojo iwenumo: ki o fo aso re, ki o si fi omi we ara re: yoo si di mimo. |
Tó o bá ṣẹ ẹnì kan , gbà pé o jẹ̀bi , kó o sì tètè tọrọ àforíjì . | To o ba se eni kan , gba pe o jebi , ko o si tete toro aforiji . |
Iṣẹ́ | Ise |
Torí náà , Ọlọ́run kọ́ ló dá ìkóbìnrinjọ sílẹ̀ , kò sì fún wọn níṣìírí láti máa ṣe é , kàkà bẹ́ẹ̀ ó fún wọn lófin tí kò ní jẹ́ kí wọ́n ki àṣejù bọ̀ ọ́ . | Tori naa , Olorun ko lo da ikobinrinjo sile , ko si fun won nisiiri lati maa se e , kaka bee o fun won lofin ti ko ni je ki won ki aseju bo o . |
Yàtọ̀ síyẹn , ọkọ kan lè sọ fún ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí pé kò gbọ́dọ̀ kọ́ àwọn ọmọ òun lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ . | Yato siyen , oko kan le so fun iyawo re to je Elerii pe ko gbodo ko awon omo oun lekoo otito . |
tẹjú | teju |
rẹ, Ọgá Ogo àti Ọlá nlá. | re, Oga Ogo ati Ola nla. |
Beatriz Gimeno Reinoso (a bi 9 May 1962, Madrid ) [1] jẹ oloselu Orile ede Spain kan ati olugboja ẹtọ LGBT . | Beatriz Gimeno Reinoso (a bi 9 May 1962, Madrid ) [1] je oloselu Orile ede Spain kan ati olugboja eto LGBT . |
Ṣùgbọ́n Pétérù dá a lóhùn wí pé, Kí owó rẹ ṣègbé pẹ̀lú rẹ, nítorí tí ìwọ rò láti fi owó ra ẹ̀bùn Ọlọ́run! Ìwọ kò ni ipa tàbí ìpín nínú ọ̀ràn yìí, nítorí ọkàn rẹ kò ṣe déedé níwájú Ọlọ́run | Sugbon Peteru da a lohun wi pe, Ki owo re segbe pelu re, nitori ti iwo ro lati fi owo ra ebun Olorun! Iwo ko ni ipa tabi ipin ninu oran yii, nitori okan re ko se deede niwaju Olorun |
Ọba wí pé, “Ta ni ó wà nínú àgbàlá?” Nísinsin yìí, Hamani ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ àgbàlá ìta ààfin ni láti sọ fún ọba nípa síso Mordekai lórí igi tí ó ti rì fún un. | Oba wi pe, "Ta ni o wa ninu agbala?" Nisinsin yii, Hamani sese wo agbala ita aafin ni lati so fun oba nipa siso Mordekai lori igi ti o ti ri fun un. |
93. Àwọn tí wòn pe Ṣuaib | 93. Awon ti won pe Suaib |
Takọtabo ẹyẹ náà ló máa ń sàba lórí ẹyin , àwọn méjèèjì ló sì máa ń fún àwọn òròmọ wọn lóúnjẹ . | Takotabo eye naa lo maa n saba lori eyin , awon mejeeji lo si maa n fun awon oromo won lounje . |
Nínú ìgbàgbọ́ àti pẹ̀lú ìdánilójú ìtìlẹ́yìn Ọlọ́run , Bárákì kó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá àwọn ọmọ ogun tí wọn ò fi bẹ́ẹ̀ mọ ogun jà lọ sójú ogun , ó sì ṣẹ́gun agbo ọmọ ogun Jábínì tí wọ́n pọ̀ gan - an lábẹ́ ìdarí Sísérà . | Ninu igbagbo ati pelu idaniloju itileyin Olorun , Baraki ko egberun mewaa awon omo ogun ti won o fi bee mo ogun ja lo soju ogun , o si segun agbo omo ogun Jabini ti won po gan - an labe idari Sisera . |
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é . | Awa Elerii Jehofa la se e . |
Bíbélì sọ ojú abẹ níkòó , nígbà tó sọ pé : “ Èrò ọkàn - àyà ènìyàn jẹ́ búburú láti ìgbà èwe rẹ̀ wá . ” | Bibeli so oju abe nikoo , nigba to so pe : " Ero okan - aya eniyan je buburu lati igba ewe re wa . " |
Ó lè dẹni tá a sún dé ọ̀nà ìparun bíi ti Sọ́ọ̀lù . | O le deni ta a sun de ona iparun bii ti Soolu . |
Lára àwọn tí mo bá ṣèkẹ́kọ̀ọ́ , méjìléláàádọ́ta ló ti ya ìgbésí ayé wọn sí mímọ́ fún Jèhófà Ọlọ́run , méjìdínláàádọ́ta sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ lára àwọn tí Marion ti bá ṣèkẹ́kọ̀ọ́ . | Lara awon ti mo ba sekekoo , mejilelaaadota lo ti ya igbesi aye won si mimo fun Jehofa Olorun , mejidinlaaadota si ti se bee lara awon ti Marion ti ba sekekoo . |
Kí lo máa sọ ? Ọ̀kẹ́ àìmọye èèyàn tó máa ń lọ sí ṣọ́ọ̀ṣì ló máa dáhùn pé , “ Bẹ́ẹ̀ ni ! ” | Ki lo maa so ? Oke aimoye eeyan to maa n lo si soosi lo maa dahun pe , “ Bee ni ! ” |
Ohun táwa náà ń ṣe nìyẹn nígbà tá a bá ń bá a lọ ní fífi òtítọ́ tá a ti kọ́ sílò . | Ohun tawa naa n se niyen nigba ta a ba n ba a lo ni fifi otito ta a ti ko silo . |
2 , 3 . ( a ) Ànímọ́ wo ló yẹ káwọn olórí Ísírẹ́lì ní , àmọ́ kí ni wọ́n ń ṣe ní ti gidi ? | 2 , 3 . ( a ) Animo wo lo ye kawon olori Isireli ni , amo ki ni won n se ni ti gidi ? |
Òun yìí ni òjíṣẹ́ ní ilé ìsìn tí ó mọ́ jùlọ tíí ṣe àgọ́ tòótọ́, tí Oluwa fúnrarẹ̀ kọ́, kì í ṣe èyí tí eniyan kọ́. | Oun yii ni ojise ni ile isin ti o mo julo tii se ago tooto, ti Oluwa funrare ko, ki i se eyi ti eniyan ko. |
Ti Ọlọ́run ni àwa ẹni tí ó bá mọ Ọlọ́run, ó ń gbọ́ tiwa | Ti Olorun ni awa eni ti o ba mo Olorun, o n gbo tiwa |
nígbà tí mo bá pọ́n idà dídán miàti tí mo bá sì fi ọwọ́ mi lé ìdájọ́,Èmi yóò san ẹ̀san fún àwọn ọ̀tá miÈmi kò sì san fún àwọn tí ó kórìíra à mi. | nigba ti mo ba pon ida didan miati ti mo ba si fi owo mi le idajo,Emi yoo san esan fun awon ota miEmi ko si san fun awon ti o koriira a mi. |
N óo tú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dà sórí ilẹ̀ ati sórí àwọn òkè, gbogbo ipadò yóo sì kún fún ẹ̀jẹ̀ rẹ̀. | N oo tu eje re da sori ile ati sori awon oke, gbogbo ipado yoo si kun fun eje re. |
ÀPỌ́SÍTÉLÌ PỌ́Ọ̀LÙ kọ̀wé sí àwọn Kristẹni tó wà láyé nígbà tí ọ̀rúndún kìíní ń parí lọ pé : “ Ẹ máa ṣọ́ra . ” | APOSITELI POOLU kowe si awon Kristeni to wa laye nigba ti orundun kiini n pari lo pe : “ E maa sora . ” |
Ẹ̀kọ́ Tá A Rí Kọ́ : | Eko Ta A Ri Ko : |
Ǹjẹ́ Ìṣọ̀kan Kristẹni Ń Béèrè Pé Kí Ìpinnu Àwọn Kristẹni Dọ́gba ? | Nje Isokan Kristeni N Beere Pe Ki Ipinnu Awon Kristeni Dogba ? |
Kí ìbùkún Rẹ̀ wà lóri àwọn ènìyàn Rẹ̀ | Ki ibukun Re wa lori awon eniyan Re |
ikẹ | ike |
Torí náà , ó gbà pé Ọlọ́run ló fa àwọn ìṣòro tí òun ní , bẹ́ẹ̀ ọ̀rọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀ . | Tori naa , o gba pe Olorun lo fa awon isoro ti oun ni , bee oro ko ri bee . |
“ Ewu Tó Dojú Kọ Ìlera Gbogbo Ènìyàn ” | " Ewu To Doju Ko Ilera Gbogbo Eniyan " |
pa ayé mí mọ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ | pa aye mi mo gege bi oro Re |
Òkè yẹn wà ní orílẹ̀ - èdè Tọ́kì lóde òní . | Oke yen wa ni orile - ede Toki lode oni . |
Ó sì rí Júù kan tí a ń pè ní Akuila, tí a bí ni Pọntu, tí ó ti Itali dé ní lọ́ọ́lọ́ọ́, pẹ̀lú Priskilla aya rẹ̀; nítorí tí Kilaudiu pàṣẹ pé, kí gbogbo àwọn Júù jáde kúrò ní Romu. Ó sì tọ̀ wọ́n lọ láti rí wọn. | O si ri Juu kan ti a n pe ni Akuila, ti a bi ni Pontu, ti o ti Itali de ni looloo, pelu Priskilla aya re; nitori ti Kilaudiu pase pe, ki gbogbo awon Juu jade kuro ni Romu. O si to won lo lati ri won. |
(ṣe) àyàfi àwọn tí wọn ní oríire tò | (se) ayafi awon ti won ni oriire to |
Àti nísisìyí, ó sì ṣe, nígbàtí ó | Ati nisisiyi, o si se, nigbati o |
Ó ní kí wọ́n máa fi èdè Gẹ̀ẹ́sì bá òun ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì , ó sì ti di akéde ìhìn rere náà báyìí . | O ni ki won maa fi ede Geesi ba oun se ikekoo Bibeli , o si ti di akede ihin rere naa bayii . |
iná ati yìnyín, ati ìrì dídì,ati ẹ̀fúùfù líle tí ń mú àṣẹ rẹ̀ ṣẹ. | ina ati yinyin, ati iri didi,ati efuufu lile ti n mu ase re se. |
Ẹrú tí ẹ̀yin bá rà lè jẹ́ nínú rẹ̀ lẹ́yìn tí ẹ̀yin bá ti kọ ọ́ ní ilà, Ṣùgbọ́n àlejò àti alágbàṣe kò ni jẹ nínú rẹ̀ | Eru ti eyin ba ra le je ninu re leyin ti eyin ba ti ko o ni ila, Sugbon alejo ati alagbase ko ni je ninu re |
Bí àpẹẹrẹ , wo ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ nínú Mátíù 10 : 29 - 31 . | Bi apeere , wo oro ti Jesu so ninu Matiu 10 : 29 - 31 . |
Ó ṣe kedere pé , kì í ṣe àwọn ọmọdé nìkan ló yẹ ká máa fi ìfẹ́ àtọkànwá hàn sí . | O se kedere pe , ki i se awon omode nikan lo ye ka maa fi ife atokanwa han si . |
Aláìgbọ́n kò rí inú dídùn sí òyeṣùgbọ́n ó ní inú dídùn sí sísọ èrò tirẹ̀. | Alaigbon ko ri inu didun si oyesugbon o ni inu didun si siso ero tire. |
Bẹ́ẹ̀ ni Símírì pa gbogbo ilé Bááṣà run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó sọ sí Bááṣà nípa ọwọ́ Jéhù wòlíì | Bee ni Simiri pa gbogbo ile Baasa run, gege bi oro Oluwa ti o so si Baasa nipa owo Jehu wolii |
Kò sí bí ipò pàjáwìrì ṣe lè mú kí ètò àti ìwéwèé wọ́n yí pa dà tó , ohun kan wà tí kò lè yí pa dà , ìyẹn ni ọ̀wọ̀ tí wọ́n ní fún àwọn aláṣẹ ìjọba àtàwọn èèyàn . | Ko si bi ipo pajawiri se le mu ki eto ati iwewee won yi pa da to , ohun kan wa ti ko le yi pa da , iyen ni owo ti won ni fun awon alase ijoba atawon eeyan . |
Bó bá yá , ọ̀rọ̀ náà á tán ńlẹ̀ , àmọ́ báwo lo ṣe lè ṣe ipa tìẹ ? | Bo ba ya , oro naa a tan nle , amo bawo lo se le se ipa tie ? |
“Nítorí náà báyìí, ẹ̀yin ọmọ mi,ìbùkún ni fún àwọn tí ó pa ọ̀nà mi mọ́, | “Nitori naa bayii, eyin omo mi,ibukun ni fun awon ti o pa ona mi mo, |
10 - 12 . ( a ) Ìmọ̀ràn wo ni àpọ́sítélì Pétérù fún àwọn Kristẹni tí wọ́n ní ọkọ tàbí aya tó jẹ́ aláìgbàgbọ́ ? | 10 - 12 . ( a ) Imoran wo ni apositeli Peteru fun awon Kristeni ti won ni oko tabi aya to je alaigbagbo ? |
91. Àti pé bí ô bá jẹ̀ òkan nínú | 91. Ati pe bi o ba je okan ninu |
Àwọn ọmọ Israẹli ṣe akiyesi ojú Mose, pé ó ń kọ mànàmànà; Mose a sì máa fi aṣọ ìbòjú bo ojú rẹ̀ títí yóo fi di ìgbà tí yóo tún wọ ilé lọ láti bá OLUWA sọ̀rọ̀. | Awon omo Israeli se akiyesi oju Mose, pe o n ko manamana; Mose a si maa fi aso iboju bo oju re titi yoo fi di igba ti yoo tun wo ile lo lati ba OLUWA soro. |
Ìgbà wo ni Dáfídì àtàwọn èèyàn rẹ̀ ṣaláìní oúnjẹ àti ohun mímu , ìrànwọ́ wo sì ni wọ́n rí gbà ? | Igba wo ni Dafidi atawon eeyan re salaini ounje ati ohun mimu , iranwo wo si ni won ri gba ? |
Ẹ jẹ́ kí àwa náà ṣe bíi tirẹ̀ ! | E je ki awa naa se bii tire ! |
Àpẹẹrẹ mìíràn ni tàwọn ẹgbẹ́ kò - sóhun - tóbìnrin - ò - lè - ṣe , tó yí nǹkan padà fáwọn obìnrin nílẹ̀ ọlọ́làjú nípa bó ṣe jà fún wọn láti lẹ́tọ̀ọ́ àtidìbò àti àǹfààní láti relé ìwé gíga títí kan àǹfààní láti ṣe iṣẹ́ tó yááyì láwùjọ . | Apeere miiran ni tawon egbe ko - sohun - tobinrin - o - le - se , to yi nnkan pada fawon obinrin nile ololaju nipa bo se ja fun won lati letoo atidibo ati anfaani lati rele iwe giga titi kan anfaani lati se ise to yaayi lawujo . |
Ibẹ̀ ni wọ́n ti pàdé obìnrin kan tó ń jẹ́ Lìdíà “ ẹni tí ó jẹ́ olùjọsìn Ọlọ́run , ” Bíbélì sọ pé : “ Jèhófà sì ṣí ọkàn - àyà rẹ̀ sílẹ̀ láti fiyè sí ” àwọn ọ̀rọ̀ tí Pọ́ọ̀lù ń sọ . — Ìṣe 16 : 9 - 15 . | Ibe ni won ti pade obinrin kan to n je Lidia " eni ti o je olujosin Olorun , " Bibeli so pe : " Jehofa si si okan - aya re sile lati fiye si " awon oro ti Poolu n so . -- Ise 16 : 9 - 15 . |
Láìsí àní - àní , àwọn ohun àrà wọ̀nyí ló rántí nígbà tí ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run dárí rẹ̀ láti sọ àwọn ọ̀rọ̀ dáradára tó kọ lórin sínú Sáàmù ìkọkàndínlógún pé : “ Àwọn ọ̀run ń polongo ògo Ọlọ́run ; òfuurufú sì ń sọ̀rọ̀ nípa iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ . | Laisi ani - ani , awon ohun ara wonyi lo ranti nigba ti emi mimo Olorun dari re lati so awon oro daradara to ko lorin sinu Saamu ikokandinlogun pe : “ Awon orun n polongo ogo Olorun ; ofuurufu si n soro nipa ise owo re . |
Kìkì ọgọ́fà ọdún péré ló kù tí Jèhófà máa mú “ àkúnya omi wá sórí ilẹ̀ ayé láti run gbogbo ẹran ara tí ipá ìyè ń ṣiṣẹ́ nínú wọn lábẹ́ ọ̀run . ” — Jẹ́nẹ́sísì 6 : 17 . | Kiki ogofa odun pere lo ku ti Jehofa maa mu “ akunya omi wa sori ile aye lati run gbogbo eran ara ti ipa iye n sise ninu won labe orun . ” — Jenesisi 6 : 17 . |
Olúwa sọ fún Mósè pé, Sọ fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, Báyìí ni kí ẹ ṣe máa súre fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì | Oluwa so fun Mose pe, So fun Aroni ati awon omo re pe, Bayii ni ki e se maa sure fun awon omo Isireli |
Grzegorz , tá a sọ pé ó jẹ́ onímọ̀ nípa ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà , ṣe àwọn ìyípadà kan nínú ìgbésí ayé rẹ̀ . | Grzegorz , ta a so pe o je onimo nipa ero konputa , se awon iyipada kan ninu igbesi aye re . |
Ẹ jẹ́ ká tún sọ̀rọ̀ nípa kòkòrò kan tó ń jẹ́ lámilámi . | E je ka tun soro nipa kokoro kan to n je lamilami . |
Èyí yàtọ̀ sí bí àìsàn ṣe ń pa àwọn sẹ́ẹ̀lì tó sì ń mú kí ara wú tàbí kó dégbò . | Eyi yato si bi aisan se n pa awon seeli to si n mu ki ara wu tabi ko degbo . |
Mo sọ fún Francisco pé kó fún mi ní Bíbélì , ó fún mi , ó sì tún fún mi ní ìwé Otitọ ti Nsinni Lọ si Iye Aiyeraiye . | Mo so fun Francisco pe ko fun mi ni Bibeli , o fun mi , o si tun fun mi ni iwe Otito ti Nsinni Lo si Iye Aiyeraiye . |
Báwo ló ṣe yẹ kí àkókò táwọn òbí máa lò pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn pọ̀ tó ? | Bawo lo se ye ki akoko tawon obi maa lo pelu awon omo won po to ? |
OJÚ ÌWÉ 3 • ORIN : 123 , 121 | OJU IWE 3 * ORIN : 123 , 121 |
Ọmọ mi, ṣọ́ra fún ohunkohun tí ó bá kọjá eléyìí, ìwé kíkọ́ kò lópin, àkàjù ìwé a sì máa kó àárẹ̀ bá eniyan. | Omo mi, sora fun ohunkohun ti o ba koja eleyii, iwe kiko ko lopin, akaju iwe a si maa ko aare ba eniyan. |
Wo oṣù May àti June nínú kàlẹ́ńdà 2005 Calendar of Jehovah’s Witnesses . | Wo osu May ati June ninu kalenda 2005 Calendar of Jehovah's Witnesses . |
Èyí ló wá jẹ́ kó rí ojú rere àwọn Faransé àtàwọn ará Róòmù . | Eyi lo wa je ko ri oju rere awon Faranse atawon ara Roomu . |
ni agbára láti ṣe ìpalára kan fún | ni agbara lati se ipalara kan fun |
Tí a bá tún wo àwọn oníṣòwò ńláńlá lóde òní nílẹ̀ Yorùbá jákèjádò, “Ọkan ni ṣànpọ̀nná kó láwùjọ èpè” ni ọ̀rọ̀ ti Ìjẹ̀ṣà. | Ti a ba tun wo awon onisowo nlanla lode oni nile Yoruba jakejado, "Okan ni sanponna ko lawujo epe" ni oro ti Ijesa. |
Lẹ́yìn náà , lálẹ́ ọjọ́ yẹn kan náà , gbogbo àwọn àpọ́sítélì kò bá Jésù ṣọ́nà . | Leyin naa , lale ojo yen kan naa , gbogbo awon apositeli ko ba Jesu sona . |
Ó gbóṣùbà fún ìgbàgbọ́ wọn tó fẹsẹ̀ múlẹ̀ , àti bí wọ́n ṣe gbé àwọn ẹ̀kọ́ wọn karí Ìwé Mímọ́ . | O gbosuba fun igbagbo won to fese mule , ati bi won se gbe awon eko won kari Iwe Mimo . |
Ó máa ń fi wọ́n hàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan , ó máa ń fi ẹ̀tọ́ wọn dù wọ́n , kì í sì í buyì kún wọn . | O maa n fi won han gege bi eni ti ko ja mo nnkan kan , o maa n fi eto won du won , ki i si i buyi kun won . |
Àwọn ọ̀mọ̀wé ti ń lo ìdíwọ̀n àkókò yìí láti lè mọ ìgbà táwọn nǹkan ojú ọ̀run máa yọ ní apá ibì kan pàtó . | Awon omowe ti n lo idiwon akoko yii lati le mo igba tawon nnkan oju orun maa yo ni apa ibi kan pato . |
Àwọn ọkùnrin Aṣeri, àwọn tí ó ti ní ìmọ̀ ogun múra fún ogun ọ̀kẹ́ méjì (40,000). | Awon okunrin Aseri, awon ti o ti ni imo ogun mura fun ogun oke meji (40,000). |
Ọ̀kan lára àwọn tó wà nínú ìgbìmọ̀ yẹn sọ pé , àtúnṣe làwọn ẹ̀dà tuntun táwọn ṣe jáde lọ́dún 1986 jẹ́ séyìí tó ti jáde tẹ́lẹ̀ torí pé inú ẹ̀dà tuntun yìí làwọn ti dá “ Dominus [ ìyẹn ‘ Olúwa ’ ] pa dà sáwọn ibi tí Iahveh wà tẹ́lẹ̀ . ” | Okan lara awon to wa ninu igbimo yen so pe , atunse lawon eda tuntun tawon se jade lodun 1986 je seyii to ti jade tele tori pe inu eda tuntun yii lawon ti da " Dominus [ iyen ' Oluwa ' ] pa da sawon ibi ti Iahveh wa tele . " |
Ṣugbọn Peteru sẹ́, ó ní, “N kò tilẹ̀ mọ ọkunrin yìí!” | Sugbon Peteru se, o ni, "N ko tile mo okunrin yii!" |
Bákan náà , wọ́n ń rí àpẹẹrẹ àwọn òṣèré tí wọ́n fẹ́ràn gan - an , àwọn wọ̀nyí sì lágbára láti nípa lórí èrò àti ìṣe àwọn èwe tó nífẹ̀ẹ́ wọn . | Bakan naa , won n ri apeere awon osere ti won feran gan - an , awon wonyi si lagbara lati nipa lori ero ati ise awon ewe to nifee won . |
Kí ọ̀run kọrin ayọ̀, kí ayé kún fún ayọ̀,ẹ̀yin òkè, ẹ máa kọrin,nítorí, OLUWA ti tu àwọn eniyan rẹ̀ ninu,yóo ṣàánú àwọn eniyan rẹ̀ tí ìyà ń jẹ. | Ki orun korin ayo, ki aye kun fun ayo,eyin oke, e maa korin,nitori, OLUWA ti tu awon eniyan re ninu,yoo saanu awon eniyan re ti iya n je. |
Bẹ́ẹ̀ nímú ń gbọ́ tóbu | Bee nimu n gbo tobu |
Síwájú sí i , ní ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà , Jèhófà dúró ti Mósè , ó sì ń pèsè ohunkóhun tó bá nílò fún un kó lè ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ tó gbé lé e lọ́wọ́ . | Siwaju si i , ni opo odun leyin naa , Jehofa duro ti Mose , o si n pese ohunkohun to ba nilo fun un ko le saseyori lenu ise to gbe le e lowo . |
Jí - ǹ - sì aláwọ̀ búlúù làwa méjèèjì wọ̀ pẹ̀lú ṣẹ́ẹ̀tì olówùú . | Ji - n - si alawo buluu lawa mejeeji wo pelu seeti olowuu . |
Nítorí àìpé ẹ̀dá , àwa èèyàn máa ń forí gbárí nígbà míì , ìyẹn sì lè mú ẹlòmíì kọsẹ̀ . | Nitori aipe eda , awa eeyan maa n fori gbari nigba mii , iyen si le mu elomii kose . |
“Nígbà tí mo jáde la àárín ìlú lọ sí ẹnu ibodè,nígbà tí mo tẹ́ ìtẹ́ mi ní ìgboro, | "Nigba ti mo jade la aarin ilu lo si enu ibode,nigba ti mo te ite mi ni igboro, |
fáfitì ilé-ìwé ìmọ̀ nípa lìngúsíìkì | fafiti ile-iwe imo nipa lingusiiki |
Má ṣe retí ohun tó pọ̀ jù ; bó bá ṣe ń dàgbà , o lè bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ọ láti ṣe púpọ̀ sí i ní bíbójú tó ìmọ́tótó ara rẹ̀ , láti tọ́jú yàrá rẹ̀ , láti máa tètè dé síbi tí wọ́n bá pè é sí àti láti máa fọwọ́ pàtàkì mú iṣẹ́ ilé ẹ̀kọ́ . | Ma se reti ohun to po ju ; bo ba se n dagba , o le bere si i ko o lati se pupo si i ni biboju to imototo ara re , lati toju yara re , lati maa tete de sibi ti won ba pe e si ati lati maa fowo pataki mu ise ile eko . |
Ìgbàgbọ́ rẹ̀ lágbára débi pé ó jẹ́ kí àwọn wòlíì Báálì yẹn kọ́kọ́ ké pe òrìṣà wọn . | Igbagbo re lagbara debi pe o je ki awon wolii Baali yen koko ke pe orisa won . |
Nítorí náà , ó ṣe kedere pé Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun ní ìdí tó lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀ láti dá orúkọ Ọlọ́run , ìyẹn Jèhófà padà sáyè rẹ̀ nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì . | Nitori naa , o se kedere pe Iwe Mimo ni Itumo Aye Tuntun ni idi to lese nle lati da oruko Olorun , iyen Jehofa pada saye re ninu Iwe Mimo Kristeni Lede Giriiki . |
Jóṣúà tó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ Mósè fẹ́ kí Mósè dá àwọn èèyàn náà lẹ́kun . | Josua to je oluranlowo Mose fe ki Mose da awon eeyan naa lekun . |
Èmi yìn ọ́ ní ìgbà méje lójúmọ́nítorí òfin òdodo rẹ. | Emi yin o ni igba meje lojumonitori ofin ododo re. |
Ẹ jẹ́ ká ṣàyẹ̀wò ọ̀nà tá a lè gbà tẹ̀ lé Jésù ká sì jàǹfààní látinú ìmọ̀ràn tó fúnni . | E je ka sayewo ona ta a le gba te le Jesu ka si janfaani latinu imoran to funni . |
Bí àpẹẹrẹ , ṣé a lè sọ pé a bọ̀wọ̀ fún wọn tá a bá lọ ń yà wọ́n ní fọ́tò láìgbàṣẹ lọ́wọ́ wọn tàbí tá ò sọ fún wọn , bóyá nígbà tí wọ́n tiẹ̀ ń jẹun lọ́wọ́ tàbí tí wọ́n ń ṣe nǹkan míì ? | Bi apeere , se a le so pe a bowo fun won ta a ba lo n ya won ni foto laigbase lowo won tabi ta o so fun won , boya nigba ti won tie n jeun lowo tabi ti won n se nnkan mii ? |
Ọtí òjò “ Saint - John’s - wort ” | Oti ojo " Saint - John's - wort " |
Ọlọ́run fúnra rẹ̀ yóò sì wà pẹ̀lú [ ìran ènìyàn ] . | Olorun funra re yoo si wa pelu [ iran eniyan ] . |
Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà;ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà rẹ. | Sugbon mo gbekele ife re ti ki i kuna;okan mi n yo ninu igbala re. |