diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ó kó àwọn ọ̀dọ́-àgùntàn ní apá rẹ̀
O ko awon odo-aguntan ni apa re
Ohun àkọ́kọ́ tí Jèhófà sọ nípa ara rẹ̀ ni pé òún jẹ́ “ Ọlọ́run aláàánú àti olóore ọ̀fẹ́ . ”
Ohun akoko ti Jehofa so nipa ara re ni pe oun je “ Olorun alaaanu ati oloore ofe . ”
( b ) Báwo ni Jèhófà ṣe ń jẹ́ ká fòye mọ ìgbà tí ìtùnú náà máa dé ?
( b ) Bawo ni Jehofa se n je ka foye mo igba ti itunu naa maa de ?
( b ) Kí ló yẹ ká máa gbàdúrà fún , kí sì nìdí ?
( b ) Ki lo ye ka maa gbadura fun , ki si nidi ?
Adura Ààbò.
Adura Aabo.
Kristẹni kan lè pinnu pé òun nílò ìbọn tóun á fi máa ṣọdẹ tàbí tóun lè fi dáàbò bo ara òun lọ́wọ́ àwọn ẹranko ẹhànnà .
Kristeni kan le pinnu pe oun nilo ibon toun a fi maa sode tabi toun le fi daabo bo ara oun lowo awon eranko ehanna .
Báwọn ìlànà tó wà lákọọ́lẹ̀ fáwọn tó wà nínú ìdílé láti máa tẹ̀ lé ò bá pọ̀ , á rọrùn láti tẹ̀ lé , èèyàn á sì lè tètè rántí wọn .
Bawon ilana to wa lakoole fawon to wa ninu idile lati maa te le o ba po , a rorun lati te le , eeyan a si le tete ranti won .
Ayé wá sú mi , mo sì gbìyànjú láti para mi .
Aye wa su mi , mo si gbiyanju lati para mi .
Rárá .
Rara .
□ tara ẹ̀ nìkan ló mọ̀ .
□ tara e nikan lo mo .
Ó hàn kedere nínú àwọn ìwé tí Banchetti kọ pé , bíi tàwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni òun náà ṣe gbà gbọ́ pé àjíǹde ti orí ilẹ̀ ayé yóò wà , gẹ́gẹ́ bí Ìwé Mímọ́ ṣe fi kọ́ni .
O han kedere ninu awon iwe ti Banchetti ko pe , bii tawon Elerii Jehofa ni oun naa se gba gbo pe ajinde ti ori ile aye yoo wa , gege bi Iwe Mimo se fi koni .
ẹ́gbẹ̀rin
egberin
Iṣẹ́ ribiribi làwọn àgbà obìnrin ń ṣe nínú ìjọ .
Ise ribiribi lawon agba obinrin n se ninu ijo .
òbìlẹ̀jẹ.?
obileje.?
Má ṣe ro tara ẹ nìkan .
Ma se ro tara e nikan .
Kò pẹ́ lẹ́yìn ìgbà yẹn ni mo gbàdúrà sí Jèhófà lálẹ́ ọjọ́ kan báyìí pé kó ràn mí lọ́wọ́ .
Ko pe leyin igba yen ni mo gbadura si Jehofa lale ojo kan bayii pe ko ran mi lowo .
Ẹ fún wa ní ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù méjì
E fun wa ni egboro ako maluu meji
Báwo ni àdúrà ti ṣe pàtàkì tó láti mú kí inú - rere - onífẹ̀ẹ́ di ọ̀kan lára àwọn ànímọ́ wa ?
Bawo ni adura ti se pataki to lati mu ki inu - rere - onifee di okan lara awon animo wa ?
Ọdún mẹ́ta kọjá kí n tó tún bẹ̀rẹ̀ sí sìn gẹ́gẹ́ bí adelé alábòójútó àyíká .
Odun meta koja ki n to tun bere si sin gege bi adele alaboojuto ayika .
'Ẹyẹkẹyẹ tú bá dorí 'kodò bí àdán
'Eyekeye tu ba dori 'kodo bi adan
Tí èrò kan bá jọ wá lójú , a máa ń sapá láti ṣe gbogbo ìwádìí tá a bá lè ṣe nípa rẹ̀ .
Ti ero kan ba jo wa loju , a maa n sapa lati se gbogbo iwadii ta a ba le se nipa re .
O fẹ́ràn gbogbo ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́,Ìwọ ẹlẹ́tàn!
O feran gbogbo oro ibaje,Iwo eletan!
Má ṣe ni alágbàṣe kan lára tí ó jẹ́ tálákà àti aláìní, bóyá ó jẹ́ arákùnrin Israẹli tàbí àlejò tí ó ń gbé ní ọ̀kan nínú àwọn ìlú rẹ.
Ma se ni alagbase kan lara ti o je talaka ati alaini, boya o je arakunrin Israeli tabi alejo ti o n gbe ni okan ninu awon ilu re.
Àjọṣe pàtàkì tó wà láàárín Jèhófà àti Ísírẹ́lì nípa tara ti dópin .
Ajose pataki to wa laaarin Jehofa ati Isireli nipa tara ti dopin .
Wọ́n rán gbogbo àwọn ìkógun sí ọba wọn ní Dámásíkọ́sì
Won ran gbogbo awon ikogun si oba won ni Damasikosi
Ìgbà tá a bá gbé ìfẹ́ àti ìgbàgbọ́ ró nínú Ọlọ́run , tá a sì ń bẹ̀rù rẹ̀ látọkànwá là ń fi hàn pé a fẹ́ dáàbò bo ẹ̀rí ọkàn wa .
Igba ta a ba gbe ife ati igbagbo ro ninu Olorun , ta a si n beru re latokanwa la n fi han pe a fe daabo bo eri okan wa .
Ni ọdun 2020 lakoko ajakale-arun Covid-19, ipilẹṣẹ Woven Threads ti ṣe ifilọlẹ ni idojukọ lori wiwakọ ile-iṣẹ naa si ọna ọrọ-aje njagun ipin ni Afirika.
Ni odun 2020 lakoko ajakale-arun Covid-19, ipilese Woven Threads ti se ifilole ni idojuko lori wiwako ile-ise naa si ona oro-aje njagun ipin ni Afirika.
Kì í kúkú ṣe ibi kan pàtó ló máa jẹ́ ojú ogun tí ogún amágẹ́dọ́nì ti máa wáyé .
Ki i kuku se ibi kan pato lo maa je oju ogun ti ogun amagedoni ti maa waye .
Bá a ṣe jíròrò rẹ̀ nínú àpilẹ̀kọ yìí , Jésù ní ìmọ̀ tó pọ̀ gan - an nípa Baba rẹ̀ ju ẹnikẹ́ni mìíràn lọ .
Ba a se jiroro re ninu apileko yii , Jesu ni imo to po gan - an nipa Baba re ju enikeni miiran lo .
Inú ẹ̀ṣẹ̀ ni wọ́n bí gbogbo wa sí .
Inu ese ni won bi gbogbo wa si .
ńípàṣẹ
nipase
Síwájú sí i , Kristẹni kan lè gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ láti ṣe ohun tó tọ́ . — Sm .
Siwaju si i , Kristeni kan le gbadura pe ki Olorun ran oun lowo lati se ohun to to . — Sm .
Àwọn Ìkookò Nínú Aṣọ Àgùntàn
Awon Ikooko Ninu Aso Aguntan
A ní láti wà lójúfò láti lè dáàbò bo ọkàn wa nípa tara . Àmọ́ wíwà lójúfò wa yóò tún légbá kan sí i , bí a óò bá dáàbò bo ọkàn ìṣàpẹẹrẹ wa kúrò lọ́wọ́ àwọn àrùn tó lè pa wá nípa tẹ̀mí .
A ni lati wa lojufo lati le daabo bo okan wa nipa tara . Amo wiwa lojufo wa yoo tun legba kan si i , bi a oo ba daabo bo okan isapeere wa kuro lowo awon arun to le pa wa nipa temi .
Ní aago mọ́kànlá ku ìṣẹ́jú mẹ́tàdínlógún òwúrọ̀ , ẹnì kan fóònù Helen , ó sì bá a sọ̀rọ̀ nípa àwọn ọmọ rẹ̀ .
Ni aago mokanla ku iseju metadinlogun owuro , eni kan foonu Helen , o si ba a soro nipa awon omo re .
Ká tiẹ̀ sọ pé ó wá pàpà lóye ẹni tó wà lẹ́yìn ìyà tó jẹ ẹ́ , ó lè máa rò ó pé kí nìdí tí Ọlọ́run fi fàyè gbà á pé kóun jẹ adúrú ìyà yẹn .
Ka tie so pe o wa papa loye eni to wa leyin iya to je e , o le maa ro o pe ki nidi ti Olorun fi faye gba a pe koun je aduru iya yen .
Irú àwọn alátakò tí ń ba tẹni jẹ́ bẹ́ẹ̀ yóò sọ ohun tí kì í ṣe òótọ́ kí wọ́n lè tan àwọn ẹlòmíràn jẹ .
Iru awon alatako ti n ba teni je bee yoo so ohun ti ki i se ooto ki won le tan awon elomiran je .
Wọ́n sì ń tipa bẹ́ẹ̀ bójú tó ìdílé wọn lọ́nà tó dára jù lọ .
Won si n tipa bee boju to idile won lona to dara ju lo .
Leila Hadioui (tí wọ́n bí ní 16 Oṣù Kínní, Ọdún 1985) jẹ́ òṣèrébìnrin, afẹwàṣiṣẹ́ àti atọ́kùn ọmọ orílẹ̀-èdè Mòrókò.
Leila Hadioui (ti won bi ni 16 Osu Kinni, Odun 1985) je oserebinrin, afewasise ati atokun omo orile-ede Moroko.
sì ní jẹ ìran kan níyà àyàfi kí A tí
si ni je iran kan niya ayafi ki A ti
Níwọ̀n bí mi ò sì ti lè gbé àpò òde ẹ̀rí , àwọn akéde mìíràn máa ń fi ìwé tí màá lò sínú àpò tiwọn nígbà tí mo bá jáde òde ẹ̀rí . ”
Niwon bi mi o si ti le gbe apo ode eri , awon akede miiran maa n fi iwe ti maa lo sinu apo tiwon nigba ti mo ba jade ode eri . "
Antônio learned that God’s Kingdom is a real heavenly government that will bring genuine peace to mankind .
Antonio learned that God’s Kingdom is a real heavenly government that will bring genuine peace to mankind .
Ohun kan ṣoṣo tí mo kábàámọ̀ níbẹ̀ ni pé mi ò jẹ́ káwọn èèyàn mi lóye ìdí tá a fi ṣèpinnu yẹn . ”
Ohun kan soso ti mo kabaamo nibe ni pe mi o je kawon eeyan mi loye idi ta a fi sepinnu yen . ”
Láàárín ẹgbẹ̀rún márùn - ún [ 5,000 ] èèyàn tó ń wáṣẹ́ , Kostas * jẹ́ ọ̀kan lára ìwọ̀nba ọgọ́rin [ 80 ] èèyàn tí wọ́n gbà síṣẹ́ ní báńkì kan tó lókìkí nílẹ̀ Yúróòpù .
Laaarin egberun marun - un [ 5,000 ] eeyan to n wase , Kostas * je okan lara iwonba ogorin [ 80 ] eeyan ti won gba sise ni banki kan to lokiki nile Yuroopu .
Ìmọ̀ràn kan rèé : Ṣàkọsílẹ̀ àwọn àṣeyọrí tó o bá ṣe àti bí inú rẹ ṣe dùn tó nígbà tó o kó ara rẹ níjàánu . — Ìlànà Bíbélì : Kólósè 3 : 8 .
Imoran kan ree : Sakosile awon aseyori to o ba se ati bi inu re se dun to nigba to o ko ara re nijaanu . -- Ilana Bibeli : Kolose 3 : 8 .
Arítẹnimọ̀ọ́wí, ó fi àpáàdì ràbàtà bo tirẹ̀ mọ́lẹ̀.
Aritenimoowi, o fi apaadi rabata bo tire mole.
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
AWON ODO BEERE PE
Àmọ́ , àwọn nǹkan wọ̀nyí máa tọ́jọ́ torí pé ohun tí wọ́n wà fún ni pé kí àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ìjọba Ọlọ́run lè máa tẹ̀ síwájú .
Amo , awon nnkan wonyi maa tojo tori pe ohun ti won wa fun ni pe ki awon ohun to je mo Ijoba Olorun le maa te siwaju .
Bí mo ṣe ń tẹ̀ síwájú sí i nínú ẹ̀kọ́ sáyẹ́ǹsì , bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe túbọ̀ ń ṣòro fún mi láti fara mọ́ àwọn ìgbàgbọ́ àti àṣà Hindu , lára wọn ni ìjọsìn àwọn ẹranko àti ère .
Bi mo se n te siwaju si i ninu eko sayensi , bee naa lo se tubo n soro fun mi lati fara mo awon igbagbo ati asa Hindu , lara won ni ijosin awon eranko ati ere .
"New penalty for minor offences in UAE".
"New penalty for minor offences in UAE".
Tá a bá ṣe bẹ́ẹ̀ , Jèhófà á ràn wá lọ́wọ́ , torí ó sọ pé : “ Èmi yóò fi okun fún ọ .
Ta a ba se bee , Jehofa a ran wa lowo , tori o so pe : “ Emi yoo fi okun fun o .
Gẹ́gẹ́ bí Sárà , ìyá ńlá rẹ̀ ti ṣe fún Hágárì , Rákélì mú Bílíhà , ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ fún Jékọ́bù gẹ́gẹ́ bí aya onípò kejì kí nǹkan lè rí bí Rákélì ṣe sọ ọ́ pé , “ kí èmi , àní èmi , lè ní àwọn ọmọ láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ . ”
Gege bi Sara , iya nla re ti se fun Hagari , Rakeli mu Biliha , iransebinrin re fun Jekobu gege bi aya onipo keji ki nnkan le ri bi Rakeli se so o pe , “ ki emi , ani emi , le ni awon omo lati odo re . ”
Kí ló sì máa ń ṣẹlẹ̀ tí wọ́n bá rí ewu ?
Ki lo si maa n sele ti won ba ri ewu ?
yòò rí àrídájú ohun tí Òô ti ṣe ní rere
yoo ri aridaju ohun ti Oo ti se ni rere
Ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́ Tó Ń Lo Pàǹtírí
Oko Ayokele To N Lo Pantiri
Àti nísisìyí, kíyèsĩ, njẹ́ ìwọ
Ati nisisiyi, kiyesi, nje iwo
Ó dájú pé kíka irú ìrírí bẹ́ẹ̀ lè fún ìgbẹ́kẹ̀lé wa nínú Baba wa ọ̀run lókun .
O daju pe kika iru iriri bee le fun igbekele wa ninu Baba wa orun lokun .
Ọlọ́run sì pe ìmọ́lẹ̀ náà ní “Ọ̀sán” àti òkùnkùn ní “Òru.” Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.
Olorun si pe imole naa ni "Osan" ati okunkun ni "Oru." Asale ati owuro si je ojo kin-in-ni.
Ègbé ni fún ilẹ̀ ayé àti fún òkun , nítorí Èṣù ti sọ̀ kalẹ̀ wá bá yín , ó ní ìbínú ńlá , ó mọ̀ pé sáà àkókò kúkúrú ni òun ní . ”
Egbe ni fun ile aye ati fun okun , nitori Esu ti so kale wa ba yin , o ni ibinu nla , o mo pe saa akoko kukuru ni oun ni . ”
Nígbà tí ó sì ti wí èyí tan, ó yípadà, ó sì rí Jesu dúró, kò sì mọ̀ pé Jesu ni.
Nigba ti o si ti wi eyi tan, o yipada, o si ri Jesu duro, ko si mo pe Jesu ni.
Atukọ̀ tó mọ èbúté dunjú yìí á wá dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ awakọ̀ òkun náà níbi tó máa ń jókòó sí , á sì máa tọ́ ọ sọ́nà .
Atuko to mo ebute dunju yii a wa duro segbee awako okun naa nibi to maa n jokoo si , a si maa to o sona .
Ọ̀pọ̀ ohun tí wọ́n sì ń kọ́ láwọn ilé ìwé wọ̀nyí ló ta ko àwọn ìlànà Bíbélì nípa ìwà tó yẹ kéèyàn máa hù .
Opo ohun ti won si n ko lawon ile iwe wonyi lo ta ko awon ilana Bibeli nipa iwa to ye keeyan maa hu .
Àmọ́ , kì í ṣe gbogbo nǹkan ni èèyàn lè fowó rà .
Amo , ki i se gbogbo nnkan ni eeyan le fowo ra .
Tí arákùnrin kàn kò bá fẹ́ gba àǹfààní iṣẹ́ ìsìn kankan nínú ìjọ , àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ wo la lè fi tún èrò rẹ̀ ṣe ?
Ti arakunrin kan ko ba fe gba anfaani ise isin kankan ninu ijo , awon ese Iwe Mimo wo la le fi tun ero re se ?
Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó sì yẹ fún ìtẹ́wọ́gbà, pé Jésù Kírísítì wá sí ayé láti gba ẹlẹ́sẹ̀ là
Otito ni oro naa, o si ye fun itewogba, pe Jesu Kirisiti wa si aye lati gba elese la
Serna ) , 7 / 8
Serna ) , 7 / 8
Bó O Bá Ti Dẹ́ṣẹ̀ Ńkọ́ O ?
Bo O Ba Ti Dese Nko O ?
Ẹnì kan lè ní àwọn ànímọ́ tó dára gidigidi , síbẹ̀ bí a kò bá ronú nípa ẹni yẹn a ò lè fà mọ́ ọn rárá .
Eni kan le ni awon animo to dara gidigidi , sibe bi a ko ba ronu nipa eni yen a o le fa mo on rara .
Láti inú oyún ni àwọn eniyan burúkú ti ṣìnà,láti ọjọ́ tí a ti bí wọn ni wọ́n tí ń ṣìṣe,tí wọn ń purọ́.
Lati inu oyun ni awon eniyan buruku ti sina,lati ojo ti a ti bi won ni won ti n sise,ti won n puro.
Ẹ pèsè àwọn ohun tí ó dára lọ́pọ̀lọ́pọ̀ lójú gbogbo ènìyàn .
E pese awon ohun ti o dara lopolopo loju gbogbo eniyan .
Gbogbo ìgbà táa bá ṣẹ̀ , Jèhófà là ń ṣẹ̀ sí ; síbẹ̀ , léraléra ló máa ń dárí jì wá , ó sì ń bá a nìṣó ní fífẹ́ wa .
Gbogbo igba taa ba se , Jehofa la n se si ; sibe , leralera lo maa n dari ji wa , o si n ba a niso ni fife wa .
Látinú Paléographìe latine , tí F .
Latinu Paleographie latine , ti F .
Òwe Yorùbá ni Bíbí ire kò ṣe fi owó rà
Owe Yoruba ni Bibi ire ko se fi owo ra
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 14 , 15 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 14 , 15 ]
nígbèkun
nigbekun
ISSN 0362-4331.
ISSN 0362-4331.
Látìgbà tí Eddie àti Bobby ti wà ní kékeré ni mo ti máa ń kó wọn lọ sóde ẹ̀rí .
Latigba ti Eddie ati Bobby ti wa ni kekere ni mo ti maa n ko won lo sode eri .
Kí nìdí ?
Ki nidi ?
Bí a ṣe ń sún mọ́ òpin ètò àwọn nǹkan búburú yìí , bẹ́ẹ̀ ni inú túbọ̀ ń bí Sátánì torí pé “ sáà àkókò kúkúrú ” ló kù fún un .
Bi a se n sun mo opin eto awon nnkan buburu yii , bee ni inu tubo n bi Satani tori pe " saa akoko kukuru " lo ku fun un .
Ṣé Ọjọ́ Iwájú Á Burú Ni àbí Ó Máa Dára ?
Se Ojo Iwaju A Buru Ni abi O Maa Dara ?
ìgbàgbọ sí ọjọ ìkẹhìn, A ti pésé
igbagbo si ojo ikehin, A ti pese
A kà á pé : “ Ọ̀pọ̀ lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ , nígbà tí wọ́n gbọ́ èyí , wí pé : ‘ Ọ̀rọ̀ yìí ń múni gbọ̀n rìrì ; ta ní lè fetí sí i ? ’ ”
A ka a pe : “ Opo lara awon omo eyin re , nigba ti won gbo eyi , wi pe : ‘ Oro yii n muni gbon riri ; ta ni le feti si i ? ’ ”
Kí ni díẹ̀ lára ohun tó fi hàn pé Bíbélì yàtọ̀ sí ìwé yòókù táwọn èèyàn kọ ?
Ki ni die lara ohun to fi han pe Bibeli yato si iwe yooku tawon eeyan ko ?
IndianaJones.com.
IndianaJones.com.
“ Ogunlọ́gọ̀ ńlá ” látinú gbogbo orílẹ̀ - èdè ló máa la “ ìpọ́njú ńlá ” já , ìpọ́njú ńlá yìí máa dópin nígbà tí ogun Amágẹ́dọ́nì bá bẹ̀rẹ̀ . ​ — Ìṣípayá 7 : 9 , 14 .
“ Ogunlogo nla ” latinu gbogbo orile - ede lo maa la “ iponju nla ” ja , iponju nla yii maa dopin nigba ti ogun Amagedoni ba bere . ​ — Isipaya 7 : 9 , 14 .
Ó tún wá sọ pé : “ Àmọ́ lọ́pọ̀ ìgbà tí mo bá ronú lé e lórí , mo máa ń bi ara mi pé , ‘ Ṣé ìpinnu tó tọ́ ni mo fẹ́ ṣe yìí ?
O tun wa so pe : " Amo lopo igba ti mo ba ronu le e lori , mo maa n bi ara mi pe , ' Se ipinnu to to ni mo fe se yii ?
Torí náà , àwọn ọ̀nà pàtó wo la lè gbà fàánú hàn sáwọn èèyàn ?
Tori naa , awon ona pato wo la le gba faanu han sawon eeyan ?
ọ̀rọ̀ rẹ̀ jáde sí wọn, àwọn ọ̀rọ èyí tí yíò dá wọn lẹ́jọ́ ní ọjọ́ ìkẹhìn, nítorí a ó fi wọ́n fún wọn fún ète yíyí wọn lọ́kàn padà nípa Messia òtítọ́, ẹnití wọ́n kọ̀ sílẹ̀; àti sí yíyí wọn lọ́kàn padà pé wọ́n lè ṣe láé wo iwájú mọ́ fún Messia láti wá, nítorí kò yẹ kí èyíkéyí wá, àfi tí yíò bá jẹ́ Messia èké tí yíò tan àwọnènìyàn jẹ; nítorí àfi Messia kan ni àwọn wòlĩ sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀, Messia nã sì ni ẹni tí àwọn Jũ yíò kọ̀ sílẹ̀.
oro re jade si won, awon oro eyi ti yio da won lejo ni ojo ikehin, nitori a o fi won fun won fun ete yiyi won lokan pada nipa Messia otito, eniti won ko sile; ati si yiyi won lokan pada pe won le se lae wo iwaju mo fun Messia lati wa, nitori ko ye ki eyikeyi wa, afi ti yio ba je Messia eke ti yio tan awoneniyan je; nitori afi Messia kan ni awon woli soro nipa re, Messia na si ni eni ti awon Ju yio ko sile.
ṣérésì
seresi
Bó ti wù kó rí , kò sí ẹnì kan tàbí orílẹ̀ - èdè kan tó yẹ kó hu ìwà ìbàjẹ́ .
Bo ti wu ko ri , ko si eni kan tabi orile - ede kan to ye ko hu iwa ibaje .
Ìkànìyàn ẹlẹ́ẹ̀kejì.
Ikaniyan eleekeji.
O óo jèrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ,ayọ̀ ń bẹ fún ọ, yóo sì dára fún ọ.Kí àwọn tí wọ́n ń fi ọjọ́ gégùn-ún fi gégùn-ún,àní àwọn tí wọ́n lè fi àṣẹ rú Lefiatani sókè.Ṣé òkun ni mí ni, tabi erinmi,tí ẹ fi yan olùṣọ́ tì mí?Láti inú ẹ̀yà Sebuluni, a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá-mẹ́fà (12,000).Láti inú ẹ̀yà Josẹfu a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá-mẹ́fà (12,000).Láti inú ẹ̀yà Benjamini a fi èdìdì sàmì sí ẹgbàá-mẹ́fà (12,000).Ṣugbọn oúnjẹ tí ó ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ ni èyí tí ó jẹ́ pé bí ẹnìkan bá jẹ ninu rẹ̀, olúwarẹ̀ kò ní kú. Àwọn eniyan burúkú ti dẹ okùn sílẹ̀ dè mí,ṣugbọn n kò kọ ìlànà rẹ sílẹ̀.Ọkunrin kan tún wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Uraya, ọmọ Ṣemaaya, láti ìlú Kiriati Jearimu. Òun náà sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ilẹ̀ yìí ati ilẹ̀ wa bí Jeremaya ti sọ yìí. He-who-eats-corn-meal-with-bean-fritters does not know the virtues of stew.
O oo jere ise owo re,ayo n be fun o, yoo si dara fun o.Ki awon ti won n fi ojo gegun-un fi gegun-un,ani awon ti won le fi ase ru Lefiatani soke.Se okun ni mi ni, tabi erinmi,ti e fi yan oluso ti mi?Lati inu eya Sebuluni, a fi edidi sami si egbaa-mefa (12,000).Lati inu eya Josefu a fi edidi sami si egbaa-mefa (12,000).Lati inu eya Benjamini a fi edidi sami si egbaa-mefa (12,000).Sugbon ounje ti o n ti orun sokale ni eyi ti o je pe bi enikan ba je ninu re, oluware ko ni ku. Awon eniyan buruku ti de okun sile de mi,sugbon n ko ko ilana re sile.Okunrin kan tun wa ti oruko re n je Uraya, omo Semaaya, lati ilu Kiriati Jearimu. Oun naa so asotele nipa ile yii ati ile wa bi Jeremaya ti so yii. He-who-eats-corn-meal-with-bean-fritters does not know the virtues of stew.
Lílò tí wọ́n ń lò ó láti kọ lẹ́tà ṣókí yìí máa ń dín owó tí wọ́n á ná kù , ẹnu kí wọ́n tẹ ọ̀rọ̀ náà sínú fóònù kí wọ́n sì fi ránṣẹ́ sí ara wọn ni .
Lilo ti won n lo o lati ko leta soki yii maa n din owo ti won a na ku , enu ki won te oro naa sinu foonu ki won si fi ranse si ara won ni .
“ Olè Jíjà Tó Fara Sin ”
" Ole Jija To Fara Sin "
Owó táwọn mọ̀lẹ́bí ń fún wa àti iṣẹ́ lébìrà la fi gbọ́ bùkátà ara wa fún ọdún méjì gbáko .
Owo tawon molebi n fun wa ati ise lebira la fi gbo bukata ara wa fun odun meji gbako .
A mọ̀ pé a ò mọ gbogbo nǹkan tán , torí náà , a kọ́ wọn pé kí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà .
A mo pe a o mo gbogbo nnkan tan , tori naa , a ko won pe ki won gbeke le Jehofa .
Yàtọ̀ síyẹn , wọ́n tún lè máa dọ́gbọ́n sọ pé ọ̀rẹ́ rẹ kan tí kì í ṣe ọkùnrin tàbí obìnrin bíi tìẹ lẹni tó o lè máa bá rìn tó o bá ń fẹ́ ẹni tó nírú àwọn ànímọ́ dáadáa yìí .
Yato siyen , won tun le maa dogbon so pe ore re kan ti ki i se okunrin tabi obinrin bii tie leni to o le maa ba rin to o ba n fe eni to niru awon animo daadaa yii .
iyọ́nú
iyonu
Wọ́n rí àwọn kan ní ìlú Tartu tó wà lápá gúúsù orílẹ̀ - èdè Estonia .
Won ri awon kan ni ilu Tartu to wa lapa guusu orile - ede Estonia .
Nígbà tó ṣe , ọmọbìnrin wọn àkọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìsìn aṣáájú ọ̀nà .
Nigba to se , omobinrin won akoko bere ise isin asaaju ona .