diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Àmọ́ ṣá o , àwọn nǹkan wọ̀nyí kò túmọ̀ sí pé ìgbéyàwó rẹ ti forí ṣánpọ́n nìyẹn .
Amo sa o , awon nnkan wonyi ko tumo si pe igbeyawo re ti fori sanpon niyen .
ìjìyà ti jẹ ẹ̀tọ lôrí àwọn aláìgbàgbọ.
ijiya ti je eto lori awon alaigbagbo.
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
Awon Onkawe Wa Beere Pe . . .
Wọn óo wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pada sọ́dọ̀ OLUWA; nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti fà wá ya, sibẹ yóo wò wá sàn; ó ti pa wá lára lóòótọ́, ṣugbọn yóo di ọgbẹ́ wa.
Won oo wi pe, “E wa, e je ki a pada sodo OLUWA; nitori bi o tile je pe o ti fa wa ya, sibe yoo wo wa san; o ti pa wa lara loooto, sugbon yoo di ogbe wa.
Nígbà tíyẹn bá wáyé , má ṣe gbà gbé ọ̀rọ̀ tó wà nínú Òwe 24 : 16 , tó sọ pé : “ Olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje pàápàá , yóò sì dìde dájúdájú ; ṣùgbọ́n àwọn ẹni burúkú ni a óò mú kọsẹ̀ nípasẹ̀ ìyọnu àjálù . ”
Nigba tiyen ba waye , ma se gba gbe oro to wa ninu Owe 24 : 16 , to so pe : " Olododo le subu ni igba meje paapaa , yoo si dide dajudaju ; sugbon awon eni buruku ni a oo mu kose nipase iyonu ajalu . "
Júúdà , ọmọ ìyá Jésù mìíràn kọ lẹ́tà onímìísí kan tó fi gba àwọn onígbàgbọ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ níyànjú pé kí wọ́n ja ìjà líle fún ìgbàgbọ́ .
Juuda , omo iya Jesu miiran ko leta onimiisi kan to fi gba awon onigbagbo elegbe re niyanju pe ki won ja ija lile fun igbagbo .
Wọ́n ní ìfẹ́ni oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún ara wọn .
Won ni ifeni onijelenke fun ara won .
Nínú àwọn ìran Bínúì Ṣíméhì, Ṣélémíáyà, Nátanì, Ádáyà, Mákánádébáì, Ṣásíáì, Ṣáráì, Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà, Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù
Ninu awon iran Binui Simehi, Selemiaya, Natani, Adaya, Makanadebai, Sasiai, Sarai, Asareli, Selemiaya, Semariaya, Salilumi, Amariya ati Josefu
Àwọn àjíǹde mẹ́sàn - án yìí mú ká nígbàgbọ́ nínú ohun tí Pọ́ọ̀lù sọ .
Awon ajinde mesan - an yii mu ka nigbagbo ninu ohun ti Poolu so .
Bí i yẹtí wúrà tàbí ohun ọ̀ṣọ́ ti wúrà dáradára ni ìbáwí ọlọ́gbọ́n fún etí tí ó bá fetísílẹ̀
Bi i yeti wura tabi ohun oso ti wura daradara ni ibawi ologbon fun eti ti o ba fetisile
Ashley Callie (ojo ogbon Oṣu kejila ọdun 1976 - ojo karun din logun osu keji odun 2008) jẹ oṣere ara ilu South Africa, ti a mọ julọ fun ipa rẹ gege bi Leone Haines ni Isidingo (2000-08).
Ashley Callie (ojo ogbon Osu kejila odun 1976 - ojo karun din logun osu keji odun 2008) je osere ara ilu South Africa, ti a mo julo fun ipa re gege bi Leone Haines ni Isidingo (2000-08).
Ní ẹsẹ kìíní , a kà pé : “ Aláyọ̀ ni ẹni tí a dárí ìdìtẹ̀ rẹ̀ jì , tí a bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ . ”
Ni ese kiini , a ka pe : “ Alayo ni eni ti a dari idite re ji , ti a bo ese re mole . ”
Nígbà yẹn , Ọlọ́run á ti pa gbogbo àwọn alátakò run .
Nigba yen , Olorun a ti pa gbogbo awon alatako run .
Ọlọ́run tún “ ṣètò ewéko akèrègbè kan , pé kí ó gòkè wá bo Jónà , kí ó bàa lè di ibòji lórí rẹ̀ , láti dá a nídè kúrò nínú ipò oníyọnu àjálù rẹ̀ . ”
Olorun tun “ seto eweko akeregbe kan , pe ki o goke wa bo Jona , ki o baa le di iboji lori re , lati da a nide kuro ninu ipo oniyonu ajalu re . ”
Ọ̀rọ̀ OLUWA tí Aisaya sọ ní ọdún tí ọba Ahasi kú:
Oro OLUWA ti Aisaya so ni odun ti oba Ahasi ku:
máhólì
maholi
nã sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀, wípé: Jẹ́ kí a lọ sí àwọn ibi ìhà ìsàlẹ̀ ọgbààjàrà nã, kí a sì ṣe àkíyèsí bóyá àwọn ẹ̀ka àdánidá nã ti mú èso búburú jáde pẹ̀lú.
na so fun iranse re, wipe: Je ki a lo si awon ibi iha isale ogbaajara na, ki a si se akiyesi boya awon eka adanida na ti mu eso buburu jade pelu.
Wọ́n bá wá, wọ́n bẹ̀ wọ́n. Wọ́n sìn wọ́n jáde, wọ́n bá rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n kúrò ninu ìlú.
Won ba wa, won be won. Won sin won jade, won ba ro won pe ki won kuro ninu ilu.
Níbẹ̀rẹ̀ , ó jọ pé orí lásán ló ń fọ́ dádì .
Nibere , o jo pe ori lasan lo n fo dadi .
Ìlànà nípa Kíkọ Òfin Ọlọrun Sára Òkúta.
Ilana nipa Kiko Ofin Olorun Sara Okuta.
Kí ni ìbáà ṣẹlẹ̀, tí ẹ fi níláti yára yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA bẹ́ẹ̀? Bẹ́ẹ̀ sì ni bí ẹ bá ṣe oríkunkun sí OLUWA lónìí, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni yóo bínú sí lọ́la.
Ki ni ibaa sele, ti e fi nilati yara yipada kuro lodo OLUWA bee? Bee si ni bi e ba se orikunkun si OLUWA lonii, gbogbo awon omo Israeli ni yoo binu si lola.
Jésù fi dá wa lójú pé Bàbá yóò “ fi ẹ̀mí mímọ́ fún àwọn tí ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ ! ”
Jesu fi da wa loju pe Baba yoo " fi emi mimo fun awon ti n beere lowo re ! "
Ó dá Jóòbù lójú pé ó wu Bàbá wa ọ̀run láti jí òun dìde .
O da Joobu loju pe o wu Baba wa orun lati ji oun dide .
A ò gbé apá mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí yẹ̀ wò lọ́kọ̀ọ̀kan .
A o gbe apa meteeta yii ye wo lokookan .
Ó mà ṣe o , ńṣe ló dà bíi pé ó máa ń ṣòro gan - an fáwọn èèyàn láti fi àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá ṣàríkọ́gbọ́n .
O ma se o , nse lo da bii pe o maa n soro gan - an fawon eeyan lati fi awon ohun to ti sele koja sarikogbon .
Mo kàn ń ṣe ohun tí wọ́n fẹ́ kí n ṣe ni torí kì í ṣe mí bíi pé mo sún mọ́ Ọlọ́run rárá .
Mo kan n se ohun ti won fe ki n se ni tori ki i se mi bii pe mo sun mo Olorun rara .
Àwọn méjèèjì jọ pohùn pọ̀ pé kò yẹ kí àwọn tún fi àkókò ṣòfò mọ́ , wọ́n sì pinnu láti ràn án lọ́wọ́ nílé . — Wo àpótí náà “ Rírí Ìrànlọ́wọ́ Gbà . ”
Awon mejeeji jo pohun po pe ko ye ki awon tun fi akoko sofo mo , won si pinnu lati ran an lowo nile . -- Wo apoti naa " Riri Iranlowo Gba . "
Tá a bá ń ṣe bẹ́ẹ̀ , a ò ní dà bí àwọn alágàbàgebè “ tí wọ́n ní ìrísí fífọkànsin Ọlọ́run ṣùgbọ́n tí wọ́n já sí èké ní ti agbára rẹ̀ . ”
Ta a ba n se bee , a o ni da bi awon alagabagebe “ ti won ni irisi fifokansin Olorun sugbon ti won ja si eke ni ti agbara re . ”
Láìsí àníàní , torí pé bí Jésù Kristi ṣe lo ìgbésí ayé ẹ̀ ṣàrà ọ̀tọ̀ , ó ṣe ọ̀pọ̀ ohun tá a lè kẹ́kọ̀ọ́ lára rẹ̀ .
Laisi aniani , tori pe bi Jesu Kristi se lo igbesi aye e sara oto , o se opo ohun ta a le kekoo lara re .
Obìnrin opó náà sì dá a lóhùn wí pé, “Bí Ọlọ́run rẹ ti wà, èmi kò ní àkàrà: bí kò ṣe ìkúnwọ́ ìyẹ̀fun nínú ìkòkò àti òróró díẹ̀ nínú kólòbó. Èmi ń ṣa igi díẹ̀ jọ láti kó lọ ilé, kí èmi kí ó sì pèsè rẹ̀ fún mi àti fún ọmọ mi, kí àwa lè jẹ ẹ́: kí a sì kú.”
Obinrin opo naa si da a lohun wi pe, "Bi Olorun re ti wa, emi ko ni akara: bi ko se ikunwo iyefun ninu ikoko ati ororo die ninu kolobo. Emi n sa igi die jo lati ko lo ile, ki emi ki o si pese re fun mi ati fun omo mi, ki awa le je e: ki a si ku."
yin, wọn yòò borí igba, bí
yin, won yoo bori igba, bi
nà, bí ò tilẹ̀ jẹ pé ṣíwájú eléyìí ni ẹ
na, bi o tile je pe siwaju eleyii ni e
Kí sì nìdí tó fi yẹ kó o kíyè sára nígbà tó o bá ń ka àwọn Bíbélì kan ?
Ki si nidi to fi ye ko o kiye sara nigba to o ba n ka awon Bibeli kan ?
Baaṣa kú, wọ́n sì sin ín sí Tirisa. Ela ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀.
Baasa ku, won si sin in si Tirisa. Ela omo re si gori oye leyin re.
Látàrí èyí , kò sí àní - àní pé àwọn jàǹbá oríṣiríṣi tí àṣìṣe ń ṣokùnfà yóò máa bá a lọ láti ṣẹlẹ̀ .
Latari eyi , ko si ani - ani pe awon janba orisirisi ti asise n sokunfa yoo maa ba a lo lati sele .
Ṣéyẹn wá túmọ̀ sí pé Ọlọ́run ti kádàrá ẹ̀ pé àwọn méjèèjì máa kọ lura wọn ni ?
Seyen wa tumo si pe Olorun ti kadara e pe awon mejeeji maa ko lura won ni ?
Ìwé Digest tí Olú Ọba Róòmù tó ń jẹ́ Justinian kọ lọ́dún 1468 rèé , ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé tó sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ òfin àti ẹjọ́ láyé àtijọ́
Iwe Digest ti Olu Oba Roomu to n je Justinian ko lodun 1468 ree , o si je okan lara awon iwe to soro nipa oro ofin ati ejo laye atijo
Èyí ni ètò tí a pinnu rẹ̀ fún gbogbo ayé, èyí ni ọwọ́ tí a nà jáde káàkiri gbogbo orílẹ̀ èdè
Eyi ni eto ti a pinnu re fun gbogbo aye, eyi ni owo ti a na jade kaakiri gbogbo orile ede
Ìwọ̀nba irú èyí tún ṣẹlẹ̀ láwọn ibi tó léwu , tí ilẹ̀ ti ní ìpele tó ń ri lábẹ́ ara wọn .
Iwonba iru eyi tun sele lawon ibi to lewu , ti ile ti ni ipele to n ri labe ara won .
▪ Olóde .
# Olode .
Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ènìyàn náà dákẹ́ síbẹ̀ wọn kò sì sọ ohunkóhun, láti fi fèsì, nítorí ọba ti paláṣẹ, Ẹ má ṣe dáa lóhùn
Sugbon gbogbo awon eniyan naa dake sibe won ko si so ohunkohun, lati fi fesi, nitori oba ti palase, E ma se daa lohun
Ṣugbọn OLUWA gba Israẹli là,títí ayé sì ni ìgbàlà rẹ̀.Ojú kò ní tì ọ́, bẹ́ẹ̀ ni o kò ní dààmú, títí lae.
Sugbon OLUWA gba Israeli la,titi aye si ni igbala re.Oju ko ni ti o, bee ni o ko ni daamu, titi lae.
12 , 13 . ( a ) Àwọn ọ̀nà wo làwọn ìpàdé Kristẹni gbà nílò ìkóra - ẹni - níjàánu ?
12 , 13 . ( a ) Awon ona wo lawon ipade Kristeni gba nilo ikora - eni - nijaanu ?
Síbẹ̀ , inú wa dùn láti mọ̀ pé ìgbàgbọ́ wọn dúró digbí lórí ìpìlẹ̀ tó lágbára gan - an .
Sibe , inu wa dun lati mo pe igbagbo won duro digbi lori ipile to lagbara gan - an .
Ibinu OLUWA ru sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì mú wọn rìn kiri ninu aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún títí gbogbo àwọn tí wọ́n ṣe burúkú níwájú OLUWA fi kú tán.
Ibinu OLUWA ru si awon omo Israeli, o si mu won rin kiri ninu asale fun ogoji odun titi gbogbo awon ti won se buruku niwaju OLUWA fi ku tan.
Èròjà pàtàkì tí wọ́n fi ń ṣe búrẹ́dì ni ìyẹ̀fun , irú èyí tí wọ́n ń rí lára kóró irúgbìn tí wọ́n gún tàbí tí wọ́n fi ọlọ lọ̀ .
Eroja pataki ti won fi n se buredi ni iyefun , iru eyi ti won n ri lara koro irugbin ti won gun tabi ti won fi olo lo .
Ẹ̀kẹta , ẹbọ ìràpadà Jésù kò ní jẹ́ kí ẹ̀rí ọkàn máa dá wa lẹ́bi .
Eketa , ebo irapada Jesu ko ni je ki eri okan maa da wa lebi .
Ǹjẹ́ O Máa Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbọlá fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́ ?
Nje O Maa N Mu Ipo Iwaju Ninu Bibola fun Awon Ta A Jo Je Onigbagbo ?
Ọba alágbára, ìwọ tí o fẹ́ràn òdodo,o ti fi ìdí ẹ̀tọ́ múlẹ̀;o ti dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ ati òdodo ní ilẹ̀ Jakọbu.
Oba alagbara, iwo ti o feran ododo,o ti fi idi eto mule;o ti da ejo eto ati ododo ni ile Jakobu.
‘ Fífẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin ’ túmọ̀ sí pé kéèyàn ‘ dúró digbí síbì kan . ’
‘ Fifese mule sinsin ’ tumo si pe keeyan ‘ duro digbi sibi kan . ’
Bí àpẹẹrẹ , wọ́n ṣàlàyé pé “ àwọn ọmọ Ọlọ́run ” tó wà nínú Jóòbù 38 : 7 , túmọ̀ sí “ àwùjọ àwọn áńgẹ́lì . ”
Bi apeere , won salaye pe " awon omo Olorun " to wa ninu Joobu 38 : 7 , tumo si " awujo awon angeli . "
Ọ̀nà pàtàkì wo la lè gbà máa mú ipò iwájú nínú bíbọlá fún gbogbo àwọn tó wà nínú ìjọ ?
Ona pataki wo la le gba maa mu ipo iwaju ninu bibola fun gbogbo awon to wa ninu ijo ?
Lọ́wọ́ kejì ẹ̀wẹ̀ , Jèhófà máa ń ran àwọn tó bá fi ẹ̀mí ìrònúpìwàdà padà sọ́dọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ .
Lowo keji ewe , Jehofa maa n ran awon to ba fi emi ironupiwada pada sodo re lowo .
4 Ṣé Ohun Tó Hàn Sí Ojúyòójú Nìkan Lò Ń Rí ?
4 Se Ohun To Han Si Ojuyooju Nikan Lo N Ri ?
Àsọyé fún gbogbo ènìyàn tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ : “ Ìrísí Ìran Ayé Yìí Ń Yí Padà ” bọ́ sákòókò gan - an ni .
Asoye fun gbogbo eniyan ti akori re je : " Irisi Iran Aye Yii N Yi Pada " bo sakooko gan - an ni .
KÍ LÈRÒ Ẹ ?
KI LERO E ?
Oòrùn gbígbóná janjan náà kò kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn olùfọkànsìn arìnrìn - àjò onísìn ti Ìjọ Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ilẹ̀ Gíríìsì tí iye wọ́n ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [ 25,000 ] , tí wọ́n ń tiraka láti dé ibi tí ère ìyá Jésù tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ jìngbìnnì náà wà .
Oorun gbigbona janjan naa ko ko irewesi ba awon olufokansin arinrin - ajo onisin ti Ijo Otodoosi ile Giriisi ti iye won ju egberun lona meeedogbon [ 25,000 ] , ti won n tiraka lati de ibi ti ere iya Jesu ti won se losoo jingbinni naa wa .
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni mo gbàdúrà sí Jèhófà lórí ọ̀rọ̀ yìí .
Opo igba ni mo gbadura si Jehofa lori oro yii .
14 , 15 . ( a ) Sọ àpẹẹrẹ àwọn tó tún èrò wọn ṣe nípa ojú tí wọ́n fi ń wo àwọn ẹlòmíràn . ( b ) Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ wọn ?
14 , 15 . ( a ) So apeere awon to tun ero won se nipa oju ti won fi n wo awon elomiran . ( b ) Bawo la se le te le apeere won ?
Níbẹ̀ ni ó wà títí Hẹrọdu fi kú. Èyí rí bẹ́ẹ̀ kí àsọtẹ́lẹ̀ nì lè ṣẹ pé, “Láti Ijipti ni mo ti pe ọmọ mi.”
Nibe ni o wa titi Herodu fi ku. Eyi ri bee ki asotele ni le se pe, “Lati Ijipti ni mo ti pe omo mi.”
gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ fún àgọ́, àgọ́ àjọ náà
gbogbo ohun oso fun ago, ago ajo naa
85. Ô dáhùn pé: 'Wọn n tọ ipasẹ̀
85. O dahun pe: 'Won n to ipase
Àmọ́ lọ́jọ́ kan nígbà tí Joel wà lọ́mọ ọdún mẹ́rin , Marc ọmọ wa sọ fún un pé , “ Joel , ó yá , jẹ́ kí Mọ́mì mọ̀ pé o lè ṣe é ! ”
Amo lojo kan nigba ti Joel wa lomo odun merin , Marc omo wa so fun un pe , “ Joel , o ya , je ki Momi mo pe o le se e ! ”
Ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe yìí dára púpọ̀ , àmọ́ Jósẹ́fù ṣì ní láti mọ ohun tó wà lọ́kàn wọn gan - an .
Ohun ti won fe se yii dara pupo , amo Josefu si ni lati mo ohun to wa lokan won gan - an .
fún oṣù mẹ́ta ”
fun osu meta ”
Oúnjẹ wòn
Ounje won
Àwọn ọ̀rẹ́ wa nílé náà ò fi wá sílẹ̀ , wọ́n ń kọ lẹ́tà sí wa lórí kọ̀ǹpútà , wọ́n sì ń fún wa níṣìírí pé ká máa tẹ̀ síwájú . ” ​ — Fílí .
Awon ore wa nile naa o fi wa sile , won n ko leta si wa lori konputa , won si n fun wa nisiiri pe ka maa te siwaju . " -- Fili .
Jẹ́ kí àwọn ètè irọ́ kí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́ pẹ̀lú ìgbéraga àti ìkẹ́gàn
Je ki awon ete iro ki o dake jee pelu igberaga ati ikegan
Nítorí náà, mo lòdì sí ọ àti sí àwọn odò rẹ, èmi yóò sì mú kí ilẹ̀ Ejibiti di píparun àti ahoro, pátápátá, láti Migdoli lọ dé Siene, dé ààlà ilẹ̀ Kuṣi.
Nitori naa, mo lodi si o ati si awon odo re, emi yoo si mu ki ile Ejibiti di piparun ati ahoro, patapata, lati Migdoli lo de Siene, de aala ile Kusi.
Má fìgbà kankan gbàgbé àwọn àǹfààní rẹpẹtẹ tó máa ń wá látinú kíka Bíbélì lójoojúmọ́ .
Ma figba kankan gbagbe awon anfaani repete to maa n wa latinu kika Bibeli lojoojumo .
Kí nìdí tí Sedekáyà fi tètè juwọ́ sílẹ̀ fún àwọn ọmọ aládé àti lẹ́yìn náà fún Ebedi - mélékì ?
Ki nidi ti Sedekaya fi tete juwo sile fun awon omo alade ati leyin naa fun Ebedi - meleki ?
O lè ka púpọ̀ sí i nínú ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ “ Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . ” nínú ìkànnì wa lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì , ìyẹn www.watchtower.org / ype [ Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ] Orúkọ wọn gan - an kọ́ nìyí . OHUN TÓ YẸ KÓ O RONÚ LÉ LÓRÍ
O le ka pupo si i ninu owo awon apileko “ Awon Odo Beere Pe . . . ” ninu ikanni wa lori Intaneeti , iyen www.watchtower.org / ype [ Alaye isale iwe ] Oruko won gan - an ko niyi . OHUN TO YE KO O RONU LE LORI
Ẹ jẹ́ ká fi gbogbo ọkàn wa nífẹ̀ẹ́ àwọn ará wa , kí inú wa sì máa dùn sí ìfẹ́ táwọn náà ń fi hàn sí wa .
E je ka fi gbogbo okan wa nifee awon ara wa , ki inu wa si maa dun si ife tawon naa n fi han si wa .
A máa ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀ déédéé , àmọ́ Frederick máa ń lo àwọn àkókò yìí láti máa tọ́ka sí àwọn àṣìṣe mi àti bó ṣe yẹ kí n ṣàtúnṣe gẹ́gẹ́ bí aya .
A maa n kekoo Bibeli pa po deedee , amo Frederick maa n lo awon akoko yii lati maa toka si awon asise mi ati bo se ye ki n satunse gege bi aya .
Kó bàa lè jáwọ́ nínú ohun tó ti di bárakú fún un yìí , ó ṣe ohun kan sórí kọ̀ǹpútà rẹ̀ táá jẹ́ kí kọ̀ǹpútà náà máa kú fúnra rẹ̀ tó bá ti di àkókò tó yẹ kó lọ sùn . — Ka Éfésù 5 : 15 , 16 .
Ko baa le jawo ninu ohun to ti di baraku fun un yii , o se ohun kan sori konputa re taa je ki konputa naa maa ku funra re to ba ti di akoko to ye ko lo sun . -- Ka Efesu 5 : 15 , 16 .
Olúwa rẹ̀, wípé: Kíni ìdí rẹ̀ tí ìwọ wá sí ibí yĩ láti gbin igi yĩ, tàbí ẹ̀ka igi yĩ? Nítorí kíyèsĩ, ọ̀gangan tí ó ṣá jùlọ nínú gbogbo ilẹ̀ ọgbà-àjàrà rẹ ni.
Oluwa re, wipe: Kini idi re ti iwo wa si ibi yi lati gbin igi yi, tabi eka igi yi? Nitori kiyesi, ogangan ti o sa julo ninu gbogbo ile ogba-ajara re ni.
A gbé ọ̀rọ̀ náà ka àwọn àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ , èyí tó wà nínú ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ ti oṣù December 15 , 2001 .
A gbe oro naa ka awon apileko fun ikekoo , eyi to wa ninu eda Ile Iso ti osu December 15 , 2001 .
Bíbélì sọ pé : “ Wọn kò sì fiyè sí i títí ìkún omi fi dé , tí ó sì gbá gbogbo wọn lọ . ” — Mátíù 24 : 39 .
Bibeli so pe : " Won ko si fiye si i titi ikun omi fi de , ti o si gba gbogbo won lo . " -- Matiu 24 : 39 .
137. Wọn sì ya apá kan sọtọ fún
137. Won si ya apa kan soto fun
Báwo la ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́ wọ̀nyí lọ́wọ́ ?
Bawo la se le ran awon odo wonyi lowo ?
Àbí ẹ ò rí nǹkan , kéèyàn fi ọ̀sẹ̀ méjì rin kìlómítà méjìlélọ́gbọ̀n [ 32 ] péré !
Abi e o ri nnkan , keeyan fi ose meji rin kilomita mejilelogbon [ 32 ] pere !
Èyí ni ọ̀rọ̀ tí àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Israẹli wí: Ìwọ àti àwọn Ìyàwó rẹ fihàn pẹ̀lú àwọn ìhùwà rẹ àti àwọn ohun tí ó ṣèlérí nígbà tí o wí pé, ‘Àwa yóò mú ẹ̀jẹ́ tí a jẹ́ ṣẹ lórí sísun tùràrí àti dída ẹbọ ohun mímu sí orí ère Ayaba Ọ̀run.’“Tẹ̀síwájú nígbà náà, ṣe ohun tí o sọ, kí o sì mú ẹ̀jẹ́ rẹ ṣẹ.
Eyi ni oro ti awon omo-ogun Olorun Israeli wi: Iwo ati awon Iyawo re fihan pelu awon ihuwa re ati awon ohun ti o seleri nigba ti o wi pe, ‘Awa yoo mu eje ti a je se lori sisun turari ati dida ebo ohun mimu si ori ere Ayaba Orun.’“Tesiwaju nigba naa, se ohun ti o so, ki o si mu eje re se.
Ṣé Èrò Ọlọ́run Ló Wà Nínú Bíbélì ?
Se Ero Olorun Lo Wa Ninu Bibeli ?
Lẹ́yìn tí Jésù ké sí Mátíù Léfì , tí í ṣe agbowó orí , pé kí ó wá di ọmọ ẹ̀yìn òun , Léfì filé pọntí , ó fọ̀nà rokà , nítorí Jésù .
Leyin ti Jesu ke si Matiu Lefi , ti i se agbowo ori , pe ki o wa di omo eyin oun , Lefi file ponti , o fona roka , nitori Jesu .
Ṣùgbọ́n a kò mú àwọn ibi gíga náà kúrò ní Ísírẹ́lì
Sugbon a ko mu awon ibi giga naa kuro ni Isireli
“ Kò sí ẹni tí ó ní ìfẹ́ tí ó tóbi ju èyí lọ , pé kí ẹnì kan fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ . ”
" Ko si eni ti o ni ife ti o tobi ju eyi lo , pe ki eni kan fi okan re lele nitori awon ore re . "
Wọ́n tẹ̀ṣíwájú láti lo àwọn ère tí Míkà ṣe, ní gbogbo àkókò tí ilé Ọlọ́run wà ní Ṣílò
Won tesiwaju lati lo awon ere ti Mika se, ni gbogbo akoko ti ile Olorun wa ni Silo
Ohun mìíràn sì tún ni pé , ó ṣeé ṣe kó ṣì máa dùn ẹ́ , tàbí kó tiẹ̀ máa dùn ẹ́ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ .
Ohun miiran si tun ni pe , o see se ko si maa dun e , tabi ko tie maa dun e ju ti tele lo .
Bó o bá fẹ́ kí tòmátì tètè pọ́n , o lè tò ó sójú fèrèsé níbi tí oòrùn á ti máa ta yẹ́ẹ́ sí i , tàbí kí o kó o sínú abọ́ àdému kan tí ò ní dá ooru púpọ̀ mú un tàbí àpòòwé tó ki tó jẹ́ aláwọ̀ kakí , kó o wá fi tòmátì kan tàbí ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹẹrẹ kan tó ti pọ́n sínú abọ́ tàbí àpòòwé náà .
Bo o ba fe ki tomati tete pon , o le to o soju ferese nibi ti oorun a ti maa ta yee si i , tabi ki o ko o sinu abo ademu kan ti o ni da ooru pupo mu un tabi apoowe to ki to je alawo kaki , ko o wa fi tomati kan tabi ogede weere kan to ti pon sinu abo tabi apoowe naa .
Pọ́ọ̀lù kọ̀wé sí àwọn Kristẹni bíi tiẹ̀ pé : “ Àwa ní gídígbò kan . . . lòdì sí àwọn olùṣàkóso ayé òkùnkùn yìí , lòdì sí àwọn agbo ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú ní àwọn ibi ọ̀run . ”
Poolu kowe si awon Kristeni bii tie pe : " Awa ni gidigbo kan . . . lodi si awon olusakoso aye okunkun yii , lodi si awon agbo omo ogun emi buruku ni awon ibi orun . "
Òun nìkanṣoṣo ni ó na ojú ọ̀run lọ, ti ó sì ń rìn lórí ìgbì òkun
Oun nikansoso ni o na oju orun lo, ti o si n rin lori igbi okun
ṣugbọn ayé, ati ìtànjẹ ọrọ̀, ati ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ mìíràn gba ọkàn wọn, ó sì fún ọ̀rọ̀ náà pa, kò sì so èso.
sugbon aye, ati itanje oro, ati ifekufee miiran gba okan won, o si fun oro naa pa, ko si so eso.
Ọba Ṣódómù sì wí fún Ábúrámù pé, Kó àwọn ènìyàn mi fún mi, ṣùgbọ́n mú àwọn ẹrù fún ara rẹ
Oba Sodomu si wi fun Aburamu pe, Ko awon eniyan mi fun mi, sugbon mu awon eru fun ara re
Títukọ̀ Lọ Dójú Ikú
Tituko Lo Doju Iku
Àwọn Bíbélì míì túmọ̀ apá yìí sí , “ bí ìlà oòrùn ṣe jìnnà sí ìwọ oòrùn . ”
Awon Bibeli mii tumo apa yii si , “ bi ila oorun se jinna si iwo oorun . ”
Ẹ̀kẹta , ìpàdé ìjọ àti lílọ sí ìpàdé déédéé .
Eketa , ipade ijo ati lilo si ipade deedee .
sìsẹ́rà
sisera
Nínú lẹ́tà tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù kọ sí àwọn Kristẹni tó jẹ́ Hébérù , ó sọ pé : “ Oúnjẹ líle jẹ́ ti àwọn ènìyàn tí ó dàgbà dénú , ti àwọn tí wọ́n tipasẹ̀ lílò kọ́ [ bíi ti eléré ìdárayá ] agbára ìwòye wọn [ Lóréfèé , “ àwọn ẹ̀yà ara tó ń jẹ́ kéèyàn ní ìmọ̀lára ” ] láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tí ó tọ́ àti ohun tí kò tọ́ . ”
Ninu leta ti apositeli Poolu ko si awon Kristeni to je Heberu , o so pe : “ Ounje lile je ti awon eniyan ti o dagba denu , ti awon ti won tipase lilo ko [ bii ti elere idaraya ] agbara iwoye won [ Lorefee , “ awon eya ara to n je keeyan ni imolara ” ] lati fi iyato saaarin ohun ti o to ati ohun ti ko to . ”
Lákòókò náà , Montano ń bá iṣẹ́ lọ lórí kíka Bíbélì náà àti ṣíṣe àtúnṣe sí i .
Lakooko naa , Montano n ba ise lo lori kika Bibeli naa ati sise atunse si i .
Ẹ̀yìn ìyẹn ló wá kó lọ sí àgbègbè mìíràn , tí àwọn Ẹlẹ́rìí kò sì mọ ibi tó ń gbé mọ́ .
Eyin iyen lo wa ko lo si agbegbe miiran , ti awon Elerii ko si mo ibi to n gbe mo .