diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ǹjẹ́ ìwọ náà lè kọ́ èdè míì , kó o lè ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ láti mọ Jèhófà ?
Nje iwo naa le ko ede mii , ko o le ran awon eeyan lowo lati mo Jehofa ?
Abẹ́rẹ́ bọ́ sómi táló; Ọ̀dọ̀fín ní òun-ún gbọ́ “jàbú!”
Abere bo somi talo; Odofin ni oun-un gbo “jabu!”
Àwọn ará Damasku bá ọ ṣòwò nítorí ọpọlọpọ ọjà ati àwọn nǹkan olówó iyebíye tí ò ń tà, wọ́n mú ọtí waini ati irun aguntan funfun wá láti Heliboni.
Awon ara Damasku ba o sowo nitori opolopo oja ati awon nnkan olowo iyebiye ti o n ta, won mu oti waini ati irun aguntan funfun wa lati Heliboni.
A máa ń fi ọrẹ ránṣẹ́ sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa ní tààràtà tàbí ká fi sínú àpótí ọrẹ tó wà ní Gbọ̀ngàn Ìjọba .
A maa n fi ore ranse si eka ofiisi wa ni taarata tabi ka fi sinu apoti ore to wa ni Gbongan Ijoba .
Nígbà tí ìṣòro dé sí wọn , ó wá hàn lóòótọ́ pé ohun tí kò ní láárí ni àwọn ọlọ́run èké wọn , àwọn ọlọ́run náà ò lè gba ara wọn sílẹ̀ , ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ pé kí wọ́n gba àwọn tó ń jọ́sìn wọn . — Oníd .
Nigba ti isoro de si won , o wa han loooto pe ohun ti ko ni laari ni awon olorun eke won , awon olorun naa o le gba ara won sile , ka ma sese wa so pe ki won gba awon to n josin won . — Onid .
Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ dojúkọ àgbàlá tí ìta
Atewo enu ona re dojuko agbala ti ita
Ní ọdún 1969 , nígbà tí mo wà ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógún [ 24 ] , ọ̀rẹ́ mi kan tó jẹ́ oníjó ní kí n wá kópa nínú ìdíje orin kíkọ kan ní ilé àrójẹ tí wọ́n ń pè ní La Rampa Azul , táwọn èèyàn mọ̀ bí ẹni mọ owó nígbà yẹn .
Ni odun 1969 , nigba ti mo wa ni omo odun merinlelogun [ 24 ] , ore mi kan to je onijo ni ki n wa kopa ninu idije orin kiko kan ni ile aroje ti won n pe ni La Rampa Azul , tawon eeyan mo bi eni mo owo nigba yen .
Nítorí pé a gbé Mahila, Tirsa, Hogla, Milka, àti Noa, àwọn ọmọbìnrin Ṣelofehadi ní ìyàwó fún àwọn ọmọ arákùnrin baba wọn.
Nitori pe a gbe Mahila, Tirsa, Hogla, Milka, ati Noa, awon omobinrin Selofehadi ni iyawo fun awon omo arakunrin baba won.
Ńṣe lọ̀rọ̀ rẹ̀ máa dà bí ẹni tó ń “ lépa ẹ̀fúùfù . ”
Nse loro re maa da bi eni to n " lepa efuufu . "
àwọn tí wọ́n pa Jesu Olúwa àti àwọn wòlíì, tí wọ́n sì tì wa jáde. Wọn kò ṣe èyí tí ó wu Ọlọ́run, wọ́n sì ṣe lòdì sí gbogbo ènìyàn
awon ti won pa Jesu Oluwa ati awon wolii, ti won si ti wa jade. Won ko se eyi ti o wu Olorun, won si se lodi si gbogbo eniyan
Rutherford , tó ń mú ipò iwájú nínú iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí àti Robert J .
Rutherford , to n mu ipo iwaju ninu ise awa Elerii ati Robert J .
Ó sọ pé kò sí òkè tó ga débi pé téèyàn bá dúró sórí rẹ̀ yóò máa rí gbogbo ìjọba ayé .
O so pe ko si oke to ga debi pe teeyan ba duro sori re yoo maa ri gbogbo ijoba aye .
Kì í ṣe àwọn ọmọdé nìkan ló fẹ́ ká gbóríyìn fáwọn ká sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ .
Ki i se awon omode nikan lo fe ka gboriyin fawon ka si fi won lokan bale .
ìwàkiwà
iwakiwa
Nífáì wá di mìmúṣẹ, gẹ́gẹ́bí a ti sọ wọ́n; nítorí ẹ kíyèsĩ, nígbàtí ó di àṣálẹ́ kò sí òkùnkùn; ẹnu sì bẹ̀rẹ̀ sí yà àwọn ènìyàn nã nítorípé kò sí òkùnkùn nígbàtí alẹ́ lẹ́.
Nifai wa di mimuse, gegebi a ti so won; nitori e kiyesi, nigbati o di asale ko si okunkun; enu si bere si ya awon eniyan na nitoripe ko si okunkun nigbati ale le.
Jésù sì ni ọkùnrin náà .
Jesu si ni okunrin naa .
Àwọn òbí rẹ tí wọ́n ń gbìyànjú láti tọ́ ọ sọ́nà kó o lè la àwọn ìṣòro líle já ni wọ́n sì dà bí atukọ̀ òkun tó mọ èbúté dunjú .
Awon obi re ti won n gbiyanju lati to o sona ko o le la awon isoro lile ja ni won si da bi atuko okun to mo ebute dunju .
Ní báyìí , wọ́n ti ní Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè Creole ti ilẹ̀ Haiti , a ò lérò pé irú ẹ̀ lè ṣẹlẹ̀ .
Ni bayii , won ti ni Iwe Mimo ni Itumo Aye Tuntun lede Creole ti ile Haiti , a o lero pe iru e le sele .
Níkẹyìn, ọkùnrin tí a fún ní tálẹ́ǹtì kan wá, ó wí pé, Olúwa, mo mọ̀ pé oǹrorò enìyàn ni ìwọ ń ṣe ìwọ ń kórè níbi tí ìwọ kò gbìn sí, ìwọ ń kó jọ níbi tí ìwọ kò ó ká sí
Nikeyin, okunrin ti a fun ni talenti kan wa, o wi pe, Oluwa, mo mo pe onroro eniyan ni iwo n se iwo n kore nibi ti iwo ko gbin si, iwo n ko jo nibi ti iwo ko o ka si
O ṣàìgbọràn sí àṣẹ OLUWA, nítorí pé, o kò pa gbogbo àwọn ará Amaleki ati àwọn nǹkan ìní wọn run. Ìdí nìyí tí OLUWA fi ṣe àwọn nǹkan wọnyi sí ọ lónìí.
O saigboran si ase OLUWA, nitori pe, o ko pa gbogbo awon ara Amaleki ati awon nnkan ini won run. Idi niyi ti OLUWA fi se awon nnkan wonyi si o lonii.
Àkọ́kọ́ ni Ìṣípayá 12 : 10 , 11 , tó sọ pé a ṣẹ́gun Èṣù , kì í ṣe nítorí ọ̀rọ̀ ìjẹ́rìí tá à ń ṣe nìkan , àmọ́ ó tún jẹ́ nítorí ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà .
Akoko ni Isipaya 12 : 10 , 11 , to so pe a segun Esu , ki i se nitori oro ijerii ta a n se nikan , amo o tun je nitori eje Odo Aguntan naa .
Nítorí ìfẹ́ ẹ̀ rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi,èmí sì ti rìn nínú òtítọ́ rẹ.
Nitori ife e re ti o duro sinsin n be niwaju mi,emi si ti rin ninu otito re.
òun ni Òrìṣà Nlá nã, òun ni ó sì dá ohun gbogbo ní ọ̀run àti ní ayé. Njẹ́ ìwọ gba èyí gbọ́ bí?
oun ni Orisa Nla na, oun ni o si da ohun gbogbo ni orun ati ni aye. Nje iwo gba eyi gbo bi?
Nítorí pé, ọkọ̀ ojú omi àwọn ilẹ̀ etídò ìwọ̀-oòrùn yóò takò ó, ọkàn rẹ̀ yóò sì pami. Nígbà náà, ni yóò padà, yóò sì bínú sí májẹ̀mú mímọ́, yóò sì padà, yóò sì fi ojúrere hàn sí àwọn tí ó kọ májẹ̀mú mímọ́ náà.
Nitori pe, oko oju omi awon ile etido iwo-oorun yoo tako o, okan re yoo si pami. Nigba naa, ni yoo pada, yoo si binu si majemu mimo, yoo si pada, yoo si fi ojurere han si awon ti o ko majemu mimo naa.
Nítorítí Olúwa kì yíò jẹ́ kí
Nitoriti Oluwa ki yio je ki
Mose wọ inú ìkùukùu náà lọ, ó gun orí òkè náà, ó sì wà níbẹ̀ fún ogoji ọjọ́, tọ̀sán-tòru.
Mose wo inu ikuukuu naa lo, o gun ori oke naa, o si wa nibe fun ogoji ojo, tosan-toru.
Ọjọ́ ìsinmi ni fún yín, ẹ gbọdọ̀ ṣẹ́ ara yín, láti ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án oṣù náà, títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ tí ó tẹ̀ lé e, ni kí ẹ fi sinmi
Ojo isinmi ni fun yin, e gbodo se ara yin, lati irole ojo kesan-an osu naa, titi di irole ojo ti o te le e, ni ki e fi sinmi
Lọ́dún 1985 , a kúrò láàárín ìlú lọ sí abúlé kan tí a ń gbé nísinsìnyí .
Lodun 1985 , a kuro laaarin ilu lo si abule kan ti a n gbe nisinsinyi .
ilẹ̀kùn
ilekun
Bí àpẹẹrẹ , nígbà tí wọ́n bá ń ṣe àwọn eré orí kọ̀ǹpútà , mo máa ń bi wọ́n bí wọn ṣe ń ṣe eré náà .
Bi apeere , nigba ti won ba n se awon ere ori konputa , mo maa n bi won bi won se n se ere naa .
Inú mi dùn gan - an láti rí ẹ̀rí yìí pé Jèhófà ti bù kún ohun tó bẹ̀rẹ̀ lọ́nà kékeré ní orílẹ̀ - èdè Bulgaria .
Inu mi dun gan - an lati ri eri yii pe Jehofa ti bu kun ohun to bere lona kekere ni orile - ede Bulgaria .
Ó tọ́ kí gbogbo àwọn èèyàn Jèhófà tí wọ́n ti ya ara wọn sí mímọ́ ní irú àfojúsùn yìí nígbà tí wọ́n bá ń wéwèé ohun tí wọ́n máa ṣe .
O to ki gbogbo awon eeyan Jehofa ti won ti ya ara won si mimo ni iru afojusun yii nigba ti won ba n wewee ohun ti won maa se .
Òǹkọ̀wé Grass ò rántí orúkọ Ẹlẹ́rìí yìí , ó sáà pè é ní ọ̀gbẹ́ni A - kì - í - ṣerú - nǹkan - bẹ́ẹ̀ .
Onkowe Grass o ranti oruko Elerii yii , o saa pe e ni ogbeni A - ki - i - seru - nnkan - bee .
4 Ohun Mẹ́rin Tó Yẹ Kó O Mọ̀ Nípa Ìkọ̀sílẹ̀
4 Ohun Merin To Ye Ko O Mo Nipa Ikosile
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé èyí tó pọ̀ jù lọ lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í nírú ìṣòro yìí , ṣùgbọ́n ní ti àwọn tó níṣòro yìí , kò sí ọ̀rọ̀ ìtùnú tó lè mú ẹ̀dùn ọkàn wọn kúrò pátápátá .
Bo tile je pe eyi to po ju lo lara awon Elerii Jehofa ki i niru isoro yii , sugbon ni ti awon to nisoro yii , ko si oro itunu to le mu edun okan won kuro patapata .
Nígbà gbogbo ni mo ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run fún oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tó fi fún un yín nínú Kírísítì Jésù
Nigba gbogbo ni mo n dupe lowo Olorun fun oore-ofe re to fi fun un yin ninu Kirisiti Jesu
Láìpẹ́ sígbà tá a wà yìí , ọjọ́ yẹn máa dé , Jèhófà á sì pa Sátánì àti gbogbo àwọn tó wà lábẹ́ àkóso rẹ̀ run .
Laipe sigba ta a wa yii , ojo yen maa de , Jehofa a si pa Satani ati gbogbo awon to wa labe akoso re run .
Kí lo lè ṣe láti dáàbò bo ara rẹ ?
Ki lo le se lati daabo bo ara re ?
Mo wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà gan - an pé kí Ọlọ́run jẹ́ kí wọ́n pè mí !
Mo wa bere si i gbadura gan - an pe ki Olorun je ki won pe mi !
Ó lé ní àádọ́rin àwọn aṣáájú nínú ìjọba tó wà níbi ìpàdé náà .
O le ni aadorin awon asaaju ninu ijoba to wa nibi ipade naa .
Réhábíà ọmọ Rẹ̀, Jéṣáíà ọmọ Rẹ̀, Jórámì ọmọ Rẹ̀
Rehabia omo Re, Jesaia omo Re, Jorami omo Re
Nígbà náà Dáfídì pa á láṣẹ fún gbogbo àwọn àgbààgbà ní Ísírẹ́lì láti ran Sólónmónì ọmọ Rẹ̀ lọ́wọ́
Nigba naa Dafidi pa a lase fun gbogbo awon agbaagba ni Isireli lati ran Solonmoni omo Re lowo
Wọn kò gbà gbọ́ pé Jèhófà mọ ohun tí wọ́n ń ṣe .
Won ko gba gbo pe Jehofa mo ohun ti won n se .
Sì wò ó, bí Olùsọ́ ẹnú ọ̀nà ilé náà ti ń gbọn àwọn pàǹtí, ó tòògbé ó sì sùn lọ, wọ́n sì wá sí àárin ilé náà, wọ́n sì ṣe bí ẹni pé wọ́n ń fẹ́ mú àlìkámà
Si wo o, bi Oluso enu ona ile naa ti n gbon awon panti, o toogbe o si sun lo, won si wa si aarin ile naa, won si se bi eni pe won n fe mu alikama
Bíbélì Elédè Púpọ̀ ti Paris ( 1629 sí 1645 ) .
Bibeli Elede Pupo ti Paris ( 1629 si 1645 ) .
Kì í ṣe àgbègbè kan péré ló ti wàásù .
Ki i se agbegbe kan pere lo ti waasu .
Pẹ̀lúpẹ̀lú Dafidi àti àwọn olórí àwọn ọmọ-ogun, ó sì yà díẹ̀ sọ́tọ̀ lára àwọn ọmọ Asafu, Hemani àti Jedutuni fún ìsìn àsọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú dùùrù, ohun èlò orin olókùn àti kimbali. Èyí sì ní àwọn iye àwọn ọkùnrin ẹni tí ó ṣe oníṣẹ́ ìsìn yìí:
Pelupelu Dafidi ati awon olori awon omo-ogun, o si ya die soto lara awon omo Asafu, Hemani ati Jedutuni fun isin asotele, pelu duuru, ohun elo orin olokun ati kimbali. Eyi si ni awon iye awon okunrin eni ti o se onise isin yii:
Farao fi kún un pé, “Ṣé ẹ̀yin náà rí i pé àwọn eniyan yìí pọ̀ pupọ ju àwọn ọmọ-ìbílẹ̀ ilẹ̀ yìí lọ, ẹ sì tún kó wọn kúrò lẹ́nu iṣẹ́ wọn?”
Farao fi kun un pe, "Se eyin naa ri i pe awon eniyan yii po pupo ju awon omo-ibile ile yii lo, e si tun ko won kuro lenu ise won?"
mú fífọ́ Rẹ̀ bọ̀ sípò, nítorí tí ó mi
mu fifo Re bo sipo, nitori ti o mi
Àwa náà lè ṣe bẹ́ẹ̀ .
Awa naa le se bee .
Ohun tí mò ń sọ yé mi o , àní mi ò fẹ́ gbé e sílẹ̀ mọ́ ni .
Ohun ti mo n so ye mi o , ani mi o fe gbe e sile mo ni .
ṣéṣíbáṣárì
sesibasari
Dafidi sì wí fún gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ó wá lọ́dọ̀ rẹ̀ ni Jerusalẹmu pé, “Ẹ dìde! Ẹ jẹ́ kí a sálọ, nítorí pé kò sí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ Absalomu; ẹ yára, kí a lọ kúrò, kí òun má bá à yára lé wa bá, kí ó má sì mú ibi bá wa, kí ó má sì fi ojú idà pa ìlú run.”
Dafidi si wi fun gbogbo awon iranse re ti o wa lodo re ni Jerusalemu pe, "E dide! E je ki a salo, nitori pe ko si eni ti yoo gba wa lowo Absalomu; e yara, ki a lo kuro, ki oun ma ba a yara le wa ba, ki o ma si mu ibi ba wa, ki o ma si fi oju ida pa ilu run."
Nígbà táwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ Jèhófà sílẹ̀ tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí jọ́sìn ère , ìwé Diutarónómì 32 : 17 sọ pé “ wọ́n ń bá a lọ láti máa rúbọ sí àwọn ẹ̀mí èṣù , kì í ṣe sí Ọlọ́run . ”
Nigba tawon omo Isireli ko Jehofa sile ti won si bere si josin ere , iwe Diutaronomi 32 : 17 so pe “ won n ba a lo lati maa rubo si awon emi esu , ki i se si Olorun . ”
Jésù fi hàn pé òun jẹ́ oníyọ̀ọ́nú nígbà tó jí ọmọbìnrin Jáírù dìde
Jesu fi han pe oun je oniyoonu nigba to ji omobinrin Jairu dide
Jèhófà Máa Ń San Èrè Rẹpẹtẹ Fáwọn Tó Ń Pa Ọ̀nà Rẹ̀ Mọ́
Jehofa Maa N San Ere Repete Fawon To N Pa Ona Re Mo
Olú : Ó kà pé : “ Inú òógùn ojú rẹ ni ìwọ yóò ti máa jẹ oúnjẹ títí tí ìwọ yóò fi padà sí ilẹ̀ , nítorí láti inú rẹ̀ ni a ti mú ọ jáde .
Olu : O ka pe : “ Inu oogun oju re ni iwo yoo ti maa je ounje titi ti iwo yoo fi pada si ile , nitori lati inu re ni a ti mu o jade .
Dájúdájú, ọjọ́ ọ̀la rẹ yóo dára,ìrètí rẹ náà kò sì ní já sí òfo.
Dajudaju, ojo ola re yoo dara,ireti re naa ko si ni ja si ofo.
Lójú àwọn kan , àṣà yìí ò burú , nǹkan àyẹ́sí lásán ni wọ́n kà á sí .
Loju awon kan , asa yii o buru , nnkan ayesi lasan ni won ka a si .
Òǹṣèwé Eugene Linden , tó gbà pé àwọn kòkòrò máa ṣẹ́gun , sọ pé : “ Àkókò tó kù fún wa láti kojú ìṣòro yìí ti kúrú gan - an . ”
Onsewe Eugene Linden , to gba pe awon kokoro maa segun , so pe : " Akoko to ku fun wa lati koju isoro yii ti kuru gan - an . "
Kì í ṣalágbàwí èrò ara rẹ̀ tàbí kó rin kinkin mọ́ ọn , bẹ́ẹ̀ ní kì í fara mọ́ èrò ti ara ẹni nípa òye Bíbélì .
Ki i salagbawi ero ara re tabi ko rin kinkin mo on , bee ni ki i fara mo ero ti ara eni nipa oye Bibeli .
sadonikísì
sadonikisi
Àwọn aṣáájú ẹ̀sìn Júù fún un láṣẹ , torí náà , ó kà á sí pé Ọlọ́run ló gbé iṣẹ́ lé òun lọ́wọ́ láti fi ẹ̀sùn kan ẹnikẹ́ni tó bá kọ̀ láti jáwọ́ nínú ẹ̀sìn Kristẹni .
Awon asaaju esin Juu fun un lase , tori naa , o ka a si pe Olorun lo gbe ise le oun lowo lati fi esun kan enikeni to ba ko lati jawo ninu esin Kristeni .
Nígbà tó yá , wọ́n yan Léopold gẹ́gẹ́ bí alábòójútó ẹ̀ka .
Nigba to ya , won yan Leopold gege bi alaboojuto eka .
Ẹlẹ́rìí Jèhófà làwọn àlejò náà .
Elerii Jehofa lawon alejo naa .
37. Ìkìlò ni fún ẹ̀dá ẹ̀nìyàn.
37. Ikilo ni fun eda eniyan.
Ó tó ohun tí àwọn ọmọ Ìjọba náà ní láti máa yọ̀ sí pé a ti yà wọ́n sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn ẹ̀sìn tó fara jọ èpò àtàwọn ẹ̀kọ́ tó ń ba àjọṣe téèyàn ní pẹ̀lú Ọlọ́run jẹ́ tó sì tún ń fa ìkọ̀sẹ̀ !
O to ohun ti awon omo Ijoba naa ni lati maa yo si pe a ti ya won soto kuro lara awon esin to fara jo epo atawon eko to n ba ajose teeyan ni pelu Olorun je to si tun n fa ikose !
Kristi kò fìgbà kankan lo àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ - èdè èyíkéyìí láti gbèjà Ìjọba náà .
Kristi ko figba kankan lo awon omo ogun orile - ede eyikeyii lati gbeja Ijoba naa .
ṣọpẹ̀.
sope.
Ẹ sọ ohun tí ẹ ní í sọ ní ọkàn - àyà yín , . . . kí ẹ sì dákẹ́ jẹ́ẹ́ . ”
E so ohun ti e ni i so ni okan - aya yin , . . . ki e si dake jee . ”
Ó kọ́ pẹpẹ ìrúbọ fún àwọn ìràwọ̀ ninu àwọn àgbàlá mejeeji tí wọ́n wà ninu ilé OLUWA.
O ko pepe irubo fun awon irawo ninu awon agbala mejeeji ti won wa ninu ile OLUWA.
Eberi ni baálé ní ìdílé Amoku,Haṣabaya ni baálé ní ìdílé Hilikaya,Netaneli ni baálé ní ìdílé Jedaaya.
Eberi ni baale ni idile Amoku,Hasabaya ni baale ni idile Hilikaya,Netaneli ni baale ni idile Jedaaya.
Èmi rán ọ ṣí wọn nísìnsìn yìí láti là wọ́n lójú, kí wọn lè yípadà kúrò nínú òkùnkùn sí ìmọ́lẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ agbára Sátanì ṣí Ọlọ́run, kí wọn lè gba ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀, àti ogún pẹ̀lú àwọn tí a sọ di mímọ̀ nípa ìgbàgbọ́ nínú mi
Emi ran o si won nisinsin yii lati la won loju, ki won le yipada kuro ninu okunkun si imole, ati kuro lowo agbara Satani si Olorun, ki won le gba idariji ese, ati ogun pelu awon ti a so di mimo nipa igbagbo ninu mi
Nígbà tí òǹkọ̀wé kan bá kọ̀wé , ó máa ṣe é lọ́nà tó fi máa wu oríṣi àwùjọ kan ní pàtó .
Nigba ti onkowe kan ba kowe , o maa se e lona to fi maa wu orisi awujo kan ni pato .
“ ‘Wo bí àwọn ọ̀tá ti mọ òkítì sí ara odi wa láti gba ìlú wa. Nítorí ogun, ìyàn ati àjàkálẹ̀ àrùn, a óo fi ìlú yìí lé àwọn ará Kalidea tí wọn gbógun tì í lọ́wọ́. Ohun tí o wí ṣẹ, o sì ti rí i.
" 'Wo bi awon ota ti mo okiti si ara odi wa lati gba ilu wa. Nitori ogun, iyan ati ajakale arun, a oo fi ilu yii le awon ara Kalidea ti won gbogun ti i lowo. Ohun ti o wi se, o si ti ri i.
Bó bá ti sọ bẹ́ẹ̀ tán àti láwọn ìgbà míì , mo máa ń gbàdúrà kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ sí Jèhófà , àlàáfíà Rẹ̀ á sì mára tù mí .
Bo ba ti so bee tan ati lawon igba mii , mo maa n gbadura kelekele si Jehofa , alaafia Re a si mara tu mi .
Ó ya èmi alára lẹ́nu , àmọ́ ó ṣe kedere pé inú àwọn èèyàn dùn láti gba ohun tí mo mú wá fún wọn .
O ya emi alara lenu , amo o se kedere pe inu awon eeyan dun lati gba ohun ti mo mu wa fun won .
Nígbà tí Juda rí i, ó rò pé panṣágà ni, nítorí ó ti bo ojú rẹ̀.
Nigba ti Juda ri i, o ro pe pansaga ni, nitori o ti bo oju re.
ẹlẹ́kọ́kànlá
elekokanla
Nítorí náà ó jẹ́ kí wọ́n rí ibinu òun,ó sì fi agbára ogun rẹ̀ hàn wọ́n.Ó tanná ràn án lọ́tùn-ún lósì, sibẹ kò yé e;iná jó o, sibẹsibẹ kò fi ṣe àríkọ́gbọ́n.ṣugbọn nígbà tí ó rí i pé mo pariwo, ó ju ẹ̀wù rẹ̀ sílẹ̀ sí mi lọ́wọ́, ó sá jáde.”Ògo ni fún ẹni tí ó lágbára láti mu yín dúró gbọningbọnin, gẹ́gẹ́ bí ìyìn rere ati iwaasu nípa Jesu Kristi ti wí ati gẹ́gẹ́ bí àdììtú tí Ọlọrun dì láti ayérayé, ṣugbọn tí ó wá tú Gbogbo àwọn ọmọ rẹ̀ lọkunrin ati lobinrin lọ láti tù ú ninu, ṣugbọn ó kọ̀, kò gba ìpẹ̀, ó ní, “Ninu ọ̀fọ̀ ni n óo wọ inú ibojì lọ bá ọmọ mi.” Bẹ́ẹ̀ ni baba rẹ̀ sọkún rẹ̀.If the fire gets at the stew, the stew will burst into speech.
Nitori naa o je ki won ri ibinu oun,o si fi agbara ogun re han won.O tanna ran an lotun-un losi, sibe ko ye e;ina jo o, sibesibe ko fi se arikogbon.sugbon nigba ti o ri i pe mo pariwo, o ju ewu re sile si mi lowo, o sa jade.”Ogo ni fun eni ti o lagbara lati mu yin duro gboningbonin, gege bi iyin rere ati iwaasu nipa Jesu Kristi ti wi ati gege bi adiitu ti Olorun di lati ayeraye, sugbon ti o wa tu Gbogbo awon omo re lokunrin ati lobinrin lo lati tu u ninu, sugbon o ko, ko gba ipe, o ni, “Ninu ofo ni n oo wo inu iboji lo ba omo mi.” Bee ni baba re sokun re.If the fire gets at the stew, the stew will burst into speech.
Ẹ wọn ibòmíràn tí òòró rẹ̀ yóo jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati ẹẹdẹgbaata (25,000) igbọnwọ (kilomita 12½), tí ìbú rẹ̀ yóo sì jẹ́ ẹgbaarun (10,000) igbọnwọ (kilomita 10). Ibẹ̀ ni yóo wà fún àwọn ọmọ Lefi tí wọn ń ṣiṣẹ́ ninu tẹmpili, ibẹ̀ ni wọn óo máa gbé.
E won ibomiran ti ooro re yoo je oke kan ati eedegbaata (25,000) igbonwo (kilomita 12 1/2), ti ibu re yoo si je egbaarun (10,000) igbonwo (kilomita 10). Ibe ni yoo wa fun awon omo Lefi ti won n sise ninu tempili, ibe ni won oo maa gbe.
Kristẹni alàgbà tó ní ẹ̀mí ìfọ̀rọ̀rora - ẹni - wò máa ń rán ara rẹ̀ létí pé : ‘ Èmi náà lè ṣe irú àṣìṣe yìí o .
Kristeni alagba to ni emi ifororora - eni - wo maa n ran ara re leti pe : ‘ Emi naa le se iru asise yii o .
Àmọ́ , torí pé a jẹ́ aláìpé , gbogbo wa la máa ń kọsẹ̀ .
Amo , tori pe a je alaipe , gbogbo wa la maa n kose .
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń jẹ́ orúkọ mọ́ Ọlọ́run , torí náà ńṣe ni wọ́n dà bí aya fún Jèhófà .
Awon omo Isireli n je oruko mo Olorun , tori naa nse ni won da bi aya fun Jehofa .
Obìnrin kan tó wá síbi ìsọ̀ náà fetí sílẹ̀ dáadáa sí àlàyé tí ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí náà ṣe fún un .
Obinrin kan to wa sibi iso naa feti sile daadaa si alaye ti okan lara awon Elerii naa se fun un .
lówùúrọ̀
lowuuro
Ìbúgbàù tó ṣẹlẹ̀ ní ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ Chernobyl ní ilẹ̀ Ukraine lọ́dún 1986 ni wọ́n ń pè lọ́pọ̀ ìgbà ní “ jàǹbá atọ́míìkì tó tíì burú jù lọ lágbàáyé . ”
Ibugbau to sele ni ile ise ero Chernobyl ni ile Ukraine lodun 1986 ni won n pe lopo igba ni " janba atomiiki to tii buru ju lo lagbaaye . "
160. Àti pé nínú, àwọn ẹ̀nìyàn
160. Ati pe ninu, awon eniyan
Ó ní “ Mo gbé , ẹ ò tíì lọ́mọ !
O ni “ Mo gbe , e o tii lomo !
Nítorí pé ó ṣe é ṣe kí a lè mú ọkọ tí kò gba Kírísítì gbọ́ súnmọ́ Ọlọ́run nípa aya tí í ṣe onígbàgbọ́, a sì le mú ìyàwó tí kò gba Kírísítì gbọ́ súnmọ́ Ọlọ́run nípa ọkọ tí í ṣe onígbàgbọ́
Nitori pe o se e se ki a le mu oko ti ko gba Kirisiti gbo sunmo Olorun nipa aya ti i se onigbagbo, a si le mu iyawo ti ko gba Kirisiti gbo sunmo Olorun nipa oko ti i se onigbagbo
“Lọ sọ fún Ebedimeleki ará Kuṣi, ‘Èyí ni ohun tí àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí: Èmi ṣetán láti mú ọ̀rọ̀ mi ṣẹ lórí ìlú yìí nípa àjálù kì í ṣe àlàáfíà. Ní àkókò náà ni yóò ṣẹ lójú rẹ.
“Lo so fun Ebedimeleki ara Kusi, ‘Eyi ni ohun ti awon omo-ogun, Olorun Israeli wi: Emi setan lati mu oro mi se lori ilu yii nipa ajalu ki i se alaafia. Ni akoko naa ni yoo se loju re.
Èmi yóò mú kí apá ọba Babeli ní agbára, èmi yóò sì fi idà mi sí ọwọ́ rẹ, ṣùgbọ́n èmi yóò ṣẹ́ apá Farao, yóò sì kérora níwájú rẹ̀ bí ọkùnrin tí a sá ní àṣápa.
Emi yoo mu ki apa oba Babeli ni agbara, emi yoo si fi ida mi si owo re, sugbon emi yoo se apa Farao, yoo si kerora niwaju re bi okunrin ti a sa ni asapa.
Ó lè jẹ́ pé Sáńbálátì fẹ́ káwọn èèyàn mọ ẹ̀sùn èké tó wà nínú lẹ́tà náà ló ṣe fi ránṣẹ́ láìlẹ̀ ẹ́ .
O le je pe Sanbalati fe kawon eeyan mo esun eke to wa ninu leta naa lo se fi ranse laile e .
kan wọ̀nyìí jẹ́ ibùgbé fún
kan wonyii je ibugbe fun
Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ;gbà mí kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá miàti àwọn onínúnibíni.
Igba mi n be ni owo re;gba mi kuro ni owo awon ota miati awon oninunibini.
Mo farabalẹ̀ fun yín,ṣugbọn kò sí ẹnikẹ́ni ninu yín tí ó lè ko Jobu lójú,kí ó sì fi àṣìṣe rẹ̀ hàn án,tabi kí ó fún un lésì àwọn àwíjàre rẹ̀.
Mo farabale fun yin,sugbon ko si enikeni ninu yin ti o le ko Jobu loju,ki o si fi asise re han an,tabi ki o fun un lesi awon awijare re.
; Méndez , N .
; Mendez , N .
Síbẹ̀ , ó dájú pé àwọn ìbùkún tí Ísírẹ́lì rí gbà pọ̀ ju ìnáwónára náà .
Sibe , o daju pe awon ibukun ti Isireli ri gba po ju inawonara naa .
Ta ló fún Èlíjà lágbára láti jí òkú dìde àti láti kojú àwọn wòlíì Báálì ?
Ta lo fun Elija lagbara lati ji oku dide ati lati koju awon wolii Baali ?
Ọ̀DỌ́MỌBÌNRIN kan tá a máa pe orúkọ rẹ̀ ní Sarah sọ ohun tó ń dùn ún .
ODOMOBINRIN kan ta a maa pe oruko re ni Sarah so ohun to n dun un .