diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Jahanama ni ibùdésí wọn. O sì jẹ̀
Jahanama ni ibudesi won. O si je
Àkọ́bí rẹ̀ lágbára bí akọ mààlúù,Ìwo rẹ̀ sì dàbí ìwo mààlúù tí ó lágbára,tí yóo fi máa ti àwọn orílẹ̀-èdè títí dé òpin ayé.Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ẹgbẹẹgbaarun àwọn ọmọ Efuraimu,ati ẹgbẹẹgbẹrun àwọn ọmọ Manase.”
Akobi re lagbara bi ako maaluu,Iwo re si dabi iwo maaluu ti o lagbara,ti yoo fi maa ti awon orile-ede titi de opin aye.Bee gege ni egbeegbaarun awon omo Efuraimu,ati egbeegberun awon omo Manase."
MÒSÁŃBÍÌKÌ
MOSANBIIKI
Ọ̀gágun MacArthur mọ ọṣẹ́ ńláǹlà tí bọ́ǹbù átọ́míìkì méjì péré ṣe nígbà tí wọ́n jù wọ́n sí ìlú Nagasaki àti Hiroshima ní ilẹ̀ Japan nígbà tí Ogun Àgbáyé Kejì ń parí lọ .
Ogagun MacArthur mo ose nlanla ti bonbu atomiiki meji pere se nigba ti won ju won si ilu Nagasaki ati Hiroshima ni ile Japan nigba ti Ogun Agbaye Keji n pari lo .
Lẹ́yìn náà igi yìí di igi ìdáná: Eniyan óo gé ninu rẹ̀, yóo fi dáná yá; yóo gé ninu rẹ̀ yóo fi dáná oúnjẹ; yóo gé ninu rẹ̀, yóo fi gbẹ́ ère, yóo máa bọ ọ́. Eniyan á wá sọ igi lásán tí ó gbẹ́ di oriṣa, á sì máa foríbalẹ̀ fún un.
Leyin naa igi yii di igi idana: Eniyan oo ge ninu re, yoo fi dana ya; yoo ge ninu re yoo fi dana ounje; yoo ge ninu re, yoo fi gbe ere, yoo maa bo o. Eniyan a wa so igi lasan ti o gbe di orisa, a si maa foribale fun un.
Ọ̀PỌ̀ ọdún lè kọjá kí òjò tó rọ̀ ní aṣálẹ̀ àríwá Chile .
OPO odun le koja ki ojo to ro ni asale ariwa Chile .
Ní ọdun kìn-ín-ní ijọba rẹ̀, èmi Dáníẹ́lì fi iyè sí i láti inú ìwé, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí wòlíì Jeremáyà, wá pé, àádọ́rin ọdún ni Jérúsálẹ́mù yóò fi wà ní ahoro
Ni odun kin-in-ni ijoba re, emi Danieli fi iye si i lati inu iwe, gege bi oro Oluwa ti wolii Jeremaya, wa pe, aadorin odun ni Jerusalemu yoo fi wa ni ahoro
Kò sí ohun tá a fẹ́ tí ò sí nínú ìwé náà , ohun tó sì wà níbẹ̀ gan - an làwa olùkọ́ àtàwọn ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́ nílò . ”
Ko si ohun ta a fe ti o si ninu iwe naa , ohun to si wa nibe gan - an lawa oluko atawon odo akekoo nilo . ”
Èmi yóò sọ àwọn ìlú yín di ahoro, èmi yóò sì ba àwọn ilé mímọ́ yín jẹ́. Èmi kì yóò sì gbọ́ òórùn dídùn yín mọ́.
Emi yoo so awon ilu yin di ahoro, emi yoo si ba awon ile mimo yin je. Emi ki yoo si gbo oorun didun yin mo.
Lóòótọ́ , ipò àwọn nǹkan nígbà táwọn òbí rẹ àgbà wà léwe lè yàtọ̀ pátápátá sí bó ṣe rí lásìkò tìrẹ .
Loooto , ipo awon nnkan nigba tawon obi re agba wa lewe le yato patapata si bo se ri lasiko tire .
Nítorí náà , mo dara pọ̀ mọ́ àwọn ọlọ́pàá Moscow tó máa ń kó àwọn tó ń ja ìjà ìgboro , èmi sì ni mò ń kọ́ àwọn ọlọ́pàá bí wọ́n ṣe máa bá àwọn arúfin wọ ìjàkadì .
Nitori naa , mo dara po mo awon olopaa Moscow to maa n ko awon to n ja ija igboro , emi si ni mo n ko awon olopaa bi won se maa ba awon arufin wo ijakadi .
Láwọn ọ̀ràn mìíràn , ìṣòro náà ni pé ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ ló ní èrò òdì nípa àwọn àgbàlagbà , wọ́n ń fojú ẹni tí kò mọ nǹkan tó ń lọ mọ́ wò wọ́n , pé èrò wọn , ohun tó jẹ́ pàtàkì sí wọn , àtàwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò bá tàwọn mu rárá .
Lawon oran miiran , isoro naa ni pe opo awon odo lo ni ero odi nipa awon agbalagba , won n foju eni ti ko mo nnkan to n lo mo wo won , pe ero won , ohun to je pataki si won , atawon ohun ti won nifee si ko ba tawon mu rara .
àkọsílẹ̀ yĩ pamọ́ sí Olúwa; àwọn àwo rẹ̀ kò ní iye lórí, nitori àṣẹ Olúwa. Nítorítí o sọ ọ́ nítọ́tọ́ pé ẹnikẹni kò gbọ́dọ̀ ní wọ́n láti ní èrè; ṣùgbọ́n àwọn àkọsílẹ̀ inú rẹ̀ jẹ iyebíye; ẹnikẹ́ni tí ó bá sì sọ ọ́ di mímọ̀, òun ni ẹnití Olúwa yíò bùkún.
akosile yi pamo si Oluwa; awon awo re ko ni iye lori, nitori ase Oluwa. Nitoriti o so o nitoto pe enikeni ko gbodo ni won lati ni ere; sugbon awon akosile inu re je iyebiye; enikeni ti o ba si so o di mimo, oun ni eniti Oluwa yio bukun.
Apá wo ló yẹ ká fọwọ́ pàtàkì mú nínú ìgbésí ayé wa ?
Apa wo lo ye ka fowo pataki mu ninu igbesi aye wa ?
Ìwádìí ti fi hàn pé , àwọn iṣẹ́ mẹ́ta pàtàkì táwọn ọlọ́pàá ń ṣe , ìyẹn lílọ káàkiri àwọn òpópónà , yíyára lọ síbi tí ìṣòro pàjáwìrì bá ti ń ṣẹlẹ̀ àti ṣíṣèwádìí lórí ìwà ọ̀daràn , kò lè mú ìwà ọ̀daràn kúrò .
Iwadii ti fi han pe , awon ise meta pataki tawon olopaa n se , iyen lilo kaakiri awon opopona , yiyara lo sibi ti isoro pajawiri ba ti n sele ati sisewadii lori iwa odaran , ko le mu iwa odaran kuro .
òkùnkùn. pé, 'Kò sí Ọlọrun
okunkun. pe, 'Ko si Olorun
Ó nígboyà débi pé nígbà tí kìnnìún kan àti béárì kan fẹ́ pa àwọn àgùntàn bàbá rẹ̀ , ó fẹ̀mí ara rẹ̀ wewu láti dáàbò bo àwọn àgùntàn náà . — 1 Sám .
O nigboya debi pe nigba ti kinniun kan ati beari kan fe pa awon aguntan baba re , o femi ara re wewu lati daabo bo awon aguntan naa . — 1 Sam .
Àjálù Mú Kí N Rí Òtítọ́
Ajalu Mu Ki N Ri Otito
kò bá ṣe pé ó na apá rẹ̀ fún ìpamọ́ àwọn bàbá wa, nwọ́n ìbá ti ṣubú sí ọwọ́ àwọn ará Lámánì, nwọ́n ìbá sì ti di ẹni ìpalára sí ìkórira wọn.
ko ba se pe o na apa re fun ipamo awon baba wa, nwon iba ti subu si owo awon ara Lamani, nwon iba si ti di eni ipalara si ikorira won.
Ọ̀pọ̀ ibi ló ti lòdì sófin láti lo àwọn oògùn kan tàbí kéèyàn ní wọn lọ́wọ́ .
Opo ibi lo ti lodi sofin lati lo awon oogun kan tabi keeyan ni won lowo .
Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì ló ń bójú tó ọ̀ràn ẹ̀kọ́ .
Soosi Katoliiki lo n boju to oran eko .
Ọ̀nà wo ló dára jù lọ tá a lè gbà lo Ìwé Mímọ́ tá a bá ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ ?
Ona wo lo dara ju lo ta a le gba lo Iwe Mimo ta a ba n ko awon eeyan lekoo ?
Oríṣiríṣi ọ̀nà ni Ọlọ́run gbà bá àwọn tó kọ Bíbélì sọ̀rọ̀ , nígbà míì , ó lè rán áńgẹ́lì sí wọn , ó sì lè bá wọn sọ̀rọ̀ lójú ìran tàbí lójú àlá .
Orisirisi ona ni Olorun gba ba awon to ko Bibeli soro , nigba mii , o le ran angeli si won , o si le ba won soro loju iran tabi loju ala .
Jesu wọ inú ọkọ̀, ó rékọjá sí òdìkejì òkun, ó bá dé ìlú ara rẹ̀.
Jesu wo inu oko, o rekoja si odikeji okun, o ba de ilu ara re.
íwọ́
iwo
Ṣugbọn pẹlu ìbúra ni, nígbà tí Ọlọrun sọ fún un pé,“Oluwa ti búra,kò ní yí ọ̀rọ̀ rẹ̀ pada:‘Ìwọ máa jẹ́ alufaa títí lae.’ ”
Sugbon pelu ibura ni, nigba ti Olorun so fun un pe,"Oluwa ti bura,ko ni yi oro re pada:'Iwo maa je alufaa titi lae.' "
àìdi
aidi
Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé àárín ìlù náà ni Òkè Aboríṣóńṣó - Bìdírẹ̀kẹ̀tẹ̀ ti Oòrùn wà .
O feree je pe aarin ilu naa ni Oke Aborisonso - Bidirekete ti Oorun wa .
( b ) Kí la máa jíròrò nínú àpilẹ̀kọ yìí ?
( b ) Ki la maa jiroro ninu apileko yii ?
Kò sí àní àní, ìyàtọ̀ gbọdọ̀ wa láàrín yín, kí àwọn tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run láàrín yín le farahàn kedere.
Ko si ani ani, iyato gbodo wa laarin yin, ki awon ti o se itewogba lodo Olorun laarin yin le farahan kedere.
Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ọ̀dọ́ , wọ́n lè ní ìfọkànbalẹ̀ pé àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí yìí kàn àwọn , ọ̀rọ̀ náà sọ pé : “ Máa ṣọ́ aláìlẹ́bi , kí o sì máa wo adúróṣánṣán , nítorí pé ọjọ́ ọ̀la ẹni yẹn yóò kún fún àlàáfíà . ” — Sáàmù 37 : 37 .
Bi won tie je odo , won le ni ifokanbale pe awon oro onimiisi yii kan awon , oro naa so pe : “ Maa so alailebi , ki o si maa wo adurosansan , nitori pe ojo ola eni yen yoo kun fun alaafia . ” — Saamu 37 : 37 .
Kó o sì tún mọ àǹfààní tí àwọn ọ̀rọ̀ yìí lè ṣe fún wa lónìí àti lọ́jọ́ iwájú .
Ko o si tun mo anfaani ti awon oro yii le se fun wa lonii ati lojo iwaju .
OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀ ó ní,
OLUWA tun ba mi soro o ni,
( b ) Àwọn ìbéèrè wo àti orí Bíbélì wo la máa gbé yẹ̀ wò ?
( b ) Awon ibeere wo ati ori Bibeli wo la maa gbe ye wo ?
fífẹ́ràn
fiferan
odidi ọdún mẹ́ta gbako láì
odidi odun meta gbako lai
Ó ṣe búburú ní ojú , gẹ́gẹ́ bí ilé Ahabu ti ṣe, Nítorí lẹ́yìn ikú baba a rẹ̀, wọ́n di olùgbani nímọ̀ràn rẹ̀ sí ṣíṣe rẹ̀.
O se buburu ni oju , gege bi ile Ahabu ti se, Nitori leyin iku baba a re, won di olugbani nimoran re si sise re.
Ǹjẹ́ kò yẹ káwa náà máa ronú lórí ìkórè tá a lè rí ní ìpínlẹ̀ ìwàásù wa , dípò ká kàn máa ronú pé aṣálẹ̀ lásán ni ?
Nje ko ye kawa naa maa ronu lori ikore ta a le ri ni ipinle iwaasu wa , dipo ka kan maa ronu pe asale lasan ni ?
Ṣùgbọ́n èmi yóò dúró ni Efesu títí dí Pentikosti.
Sugbon emi yoo duro ni Efesu titi di Pentikosti.
Àmọ́ , ojúlówó ìrètí yóò jẹ́ kí ìgbàgbọ́ wa lágbára .
Amo , ojulowo ireti yoo je ki igbagbo wa lagbara .
Ó sọ pé ńṣe ló dà bíi pé wọ́n ń fẹ́ láti mọ “ ọ̀nà àbùjá ” tí wọ́n á fi lè tètè máa yọrùn kúrò nínú ìṣòro ìdílé kí wọ́n bàa lè gbàgbé nípa rẹ̀ kí wọ́n sì pa dà sídìí iṣẹ́ wọn .
O so pe nse lo da bii pe won n fe lati mo " ona abuja " ti won a fi le tete maa yorun kuro ninu isoro idile ki won baa le gbagbe nipa re ki won si pa da sidii ise won .
Ohun Tí Bíbélì Sọ Bá Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Mu
Ohun Ti Bibeli So Ba Imo Sayensi Mu
Nígbà tí míṣọ́nnárì kan tó tún jẹ́ atukọ̀ òkun , John Williams débẹ̀ , ó rán àwọn tọkọtaya méjì pé kí wọ́n lọ kọ́ àwọn olùgbé erékùṣù Rarotonga lẹ́kọ̀ọ́ .
Nigba ti misonnari kan to tun je atuko okun , John Williams debe , o ran awon tokotaya meji pe ki won lo ko awon olugbe erekusu Rarotonga lekoo .
13 , 14 . ( a ) Ìtùnú wo ni àdúrà tí Sólómọ́nì gbà níbi ìyàsímímọ́ tẹ́ńpìlì fún ọ ?
13 , 14 . ( a ) Itunu wo ni adura ti Solomoni gba nibi iyasimimo tenpili fun o ?
Mo ronú pé mo máa kú .
Mo ronu pe mo maa ku .
Àjọ yìí ti tẹ Bíbélì àtàwọn ìwé míì tó dá lórí Bíbélì jáde ní irínwó lé mẹ́tàléláàádọ́rin [ 473 ] èdè .
Ajo yii ti te Bibeli atawon iwe mii to da lori Bibeli jade ni irinwo le metalelaaadorin [ 473 ] ede .
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Níwà Ọmọlúwàbí
Idi To Fi Ye Ka Niwa Omoluwabi
Rò ó wò ná , Ọlọ́run tí mo ti ń yán hànhàn láti mọ̀ látìgbà kékeré mi nìyí !
Ro o wo na , Olorun ti mo ti n yan hanhan lati mo latigba kekere mi niyi !
Àmọ́ òmìnira yìí tún ní ìpèníjà tirẹ̀ .
Amo ominira yii tun ni ipenija tire .
Ní ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yóò sọ ẹ̀míi wọn nù nígbà tí ilé ìṣọ́ yóò wó lulẹ̀, odò omi yóò ṣàn lórí òkè gíga àti lórí àwọn òkè kékeré
Ni ojo ti opolopo yoo so emii won nu nigba ti ile iso yoo wo lule, odo omi yoo san lori oke giga ati lori awon oke kekere
Ó ti wá ṣeé ṣe báyìí láti mú àbùdá láti ara àwọn bakitéríà , fáírọ́ọ̀sì , kòkòrò , ẹran tàbí lára àwọn èèyàn pàápàá kí wọ́n sì fi sínú ohun ọ̀gbìn . ”
O ti wa see se bayii lati mu abuda lati ara awon bakiteria , fairoosi , kokoro , eran tabi lara awon eeyan paapaa ki won si fi sinu ohun ogbin . ”
Kì í tiẹ̀ fún mi láyè láti sọ̀rọ̀ !
Ki i tie fun mi laye lati soro !
A máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn opó. Ó fẹ́ràn àwọn àlejò, a sì máa fún wọn ní oúnjẹ ati aṣọ.
A maa se idajo otito fun awon alainibaba ati awon opo. O feran awon alejo, a si maa fun won ni ounje ati aso.
okè-nla
oke-nla
Àbí ó ṣàǹfààní kéèyàn jẹ́ ẹlẹ́mìí àlàáfíà ?
Abi o sanfaani keeyan je elemii alaafia ?
( Ìsẹ 9 : 3 - 6 ) Nígbà tí Pọ́ọ̀lù wà ní Áténì ní Gíríìsì , ó sọ̀rọ̀ nípa “ Ọlọ́run tí ó dá ayé àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀ . ”
( Ise 9 : 3 - 6 ) Nigba ti Poolu wa ni Ateni ni Giriisi , o soro nipa “ Olorun ti o da aye ati gbogbo ohun ti o wa ninu re . ”
Èyí ni Olúwa Ọlọ́run wí
Eyi ni Oluwa Olorun wi
Ẹ̀mí yìí kì í ṣe Ọlọ́run rárá , ipá ìṣiṣẹ́ tí Ọlọ́run fi máa ń ṣe ohunkóhun tó bá fẹ́ ṣe ni .
Emi yii ki i se Olorun rara , ipa isise ti Olorun fi maa n se ohunkohun to ba fe se ni .
Ẹsẹ Bíbélì yìí lè jẹ́ kéèyàn mọ̀ pé Bíbélì ni orísun ìtùnú tó yẹ kóun túbọ̀ gbé yẹ̀ wò .
Ese Bibeli yii le je keeyan mo pe Bibeli ni orisun itunu to ye koun tubo gbe ye wo .
Nítòótọ́ mó ti fi ré ná, nítorí pé, ẹ̀yin kò fi sí ọkàn yín láti bu ọlá fún mi
Nitooto mo ti fi re na, nitori pe, eyin ko fi si okan yin lati bu ola fun mi
Ṣùgbọ́n jíjẹ́ ọlọ́yàyà àti híhùwà bí ọ̀rẹ́ lè pẹ̀tù sí ohun tí ì bá dá wàhálà sílẹ̀ .
Sugbon jije oloyaya ati hihuwa bi ore le petu si ohun ti i ba da wahala sile .
Jésù sọ pé : “ A ó sì wàásù ìhìn rere ìjọba yìí ní gbogbo ilẹ̀ ayé tí a ń gbé , láti ṣe ẹ̀rí fún gbogbo àwọn orílẹ̀ - èdè ; nígbà náà ni òpin yóò sì dé . ” — Mátíù 24 : 14 .
Jesu so pe : “ A o si waasu ihin rere ijoba yii ni gbogbo ile aye ti a n gbe , lati se eri fun gbogbo awon orile - ede ; nigba naa ni opin yoo si de . ” — Matiu 24 : 14 .
Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ náà tí èmi ó fi fún yín
Nigba ti e ba de ile naa ti emi o fi fun yin
Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i irú iṣẹ ti wọn nṣe ni ìdílé, oriṣiriṣi èdè ìbílẹ̀ Yorùbá, oúnjẹ ti wọn njẹ àti èyí ti wọn ki i jẹ, ẹ̀sìn ìdílé, àdúgbò ti wọ́n tẹ̀dó si tàbi ìlú ti a ti ṣẹ̀ wá, àṣeyọrí ti wọn ti ṣe ni ìran ẹni àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ
Ninu oriki ni a ti le mo itan isedale ebi eni ati ohun ti a mo idile mo, bi i iru ise ti won nse ni idile, orisirisi ede ibile Yoruba, ounje ti won nje ati eyi ti won ki i je, esin idile, adugbo ti won tedo si tabi ilu ti a ti se wa, aseyori ti won ti se ni iran eni ati be e be e lo
Ìfẹ́ Jèhófà àti ti ọmọnìkejì tí wọ́n ní lohun pàtàkì tó jẹ́ kí n lè pa dà sínú agbo Ọlọ́run . ”
Ife Jehofa ati ti omonikeji ti won ni lohun pataki to je ki n le pa da sinu agbo Olorun . "
Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí mò ń mu yín lọ, “Bí ẹnìkan bá fẹ́ rú ẹbọ alaafia, tí ó sì mú ẹran láti inú agbo ẹran rẹ̀ fún ẹbọ náà, kì báà jẹ́ akọ tabi abo, ó níláti jẹ́ èyí tí kò ní àbààwọ́n níwájú OLUWA. Nígbà tí yóo bá fi mọ bí a ti í kọ nǹkan burúkú, tí a sì í yan nǹkan rere, wàrà ati oyin ni àwọn eniyan yóo máa jẹ. pé: ta ni ô sọ ẹ̀yí fún ọ?. Òun
Nigba ti e ba de ile ti mo n mu yin lo, “Bi enikan ba fe ru ebo alaafia, ti o si mu eran lati inu agbo eran re fun ebo naa, ki baa je ako tabi abo, o nilati je eyi ti ko ni abaawon niwaju OLUWA. Nigba ti yoo ba fi mo bi a ti i ko nnkan buruku, ti a si i yan nnkan rere, wara ati oyin ni awon eniyan yoo maa je. pe: ta ni o so eyi fun o?. Oun
Ní gbogbo àsìkò yẹn , ẹ̀gbọ́n mi obìnrin máa ń wá sọ́dọ̀ mi déédéé .
Ni gbogbo asiko yen , egbon mi obinrin maa n wa sodo mi deedee .
Ńṣe làwọn èèyàn ka ìbálòpọ̀ sí ọ̀nà tí ẹ̀dá lè gbà fi ìfẹ́ni hàn , èyí téèyàn lè ṣe ní ìgbàkígbà tó bá sáà ti wù ú , wọn kò wò ó bí nǹkan tó jẹ́ pé inú ìgbéyàwó nìkan ló gbọ́dọ̀ mọ .
Nse lawon eeyan ka ibalopo si ona ti eda le gba fi ifeni han , eyi teeyan le se ni igbakigba to ba saa ti wu u , won ko wo o bi nnkan to je pe inu igbeyawo nikan lo gbodo mo .
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n díwọ̀n àwọn eré àṣedárayá “ tí ẹni méjì ń ṣọ́ ara wọn láti pa ara wọn ” nínú rẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú ọjọ́ orí ẹni tó ń ṣe eré náà , òtítọ́ ibẹ̀ ni pé wọn kì í fi bẹ́ẹ̀ lè ṣàkóso wọn .
Bo tile je pe won diwon awon ere asedaraya " ti eni meji n so ara won lati pa ara won " ninu re ni ibamu pelu ojo ori eni to n se ere naa , otito ibe ni pe won ki i fi bee le sakoso won .
Bákan náà ló ṣe yẹ kó o fẹ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ lára Kristi kó o sì máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀ .
Bakan naa lo se ye ko o fe lati kekoo lara Kristi ko o si maa te le apeere re .
Ǹjẹ́ ò ń sapá láti jèrè ìmọ̀ pípéye yẹn ?
Nje o n sapa lati jere imo pipeye yen ?
Bíbélì sọ pé èèyàn tó bá ń gbé irú ìgbé ayé bẹ́ẹ̀ , á “ dà bí igi tí a gbìn sẹ́bàá àwọn ìṣàn omi , tí ń pèsè èso tirẹ̀ ní àsìkò rẹ̀ èyí tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ eléwé kì í sì í rọ , gbogbo nǹkan tí ó bá ń ṣe ni yóò sì máa kẹ́sẹ járí . ” — Sáàmù 1 : 3 .
Bibeli so pe eeyan to ba n gbe iru igbe aye bee , a " da bi igi ti a gbin sebaa awon isan omi , ti n pese eso tire ni asiko re eyi ti awon eka re elewe ki i si i ro , gbogbo nnkan ti o ba n se ni yoo si maa kese jari . " -- Saamu 1 : 3 .
Lórí pẹ̀tẹ́lẹ̀ ti Móábù pẹ̀lú Jọ́dánì tí ó kọjá Jẹ́ríkò, Mósè àti Élíásárì àlùfáà sọ̀rọ̀ pẹ̀lú wọn ó wí pé, Ka iye àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ọmọ ogun ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti paláṣẹ fún Mósè
Lori petele ti Moabu pelu Jodani ti o koja Jeriko, Mose ati Eliasari alufaa soro pelu won o wi pe, Ka iye awon okunrin ti o je omo ogun odun tabi ju bee lo, gege bi Oluwa ti palase fun Mose
Gẹ́gẹ́ bí kìnnìún yóò fi ibùba rẹ̀ sílẹ̀, ilẹ̀ wọn yóò sì di ahoro, nítorí idà àwọn anínilára, àti nítorí ìbínú ńlá Olúwa
Gege bi kinniun yoo fi ibuba re sile, ile won yoo si di ahoro, nitori ida awon aninilara, ati nitori ibinu nla Oluwa
Bí ẹ bá ti gbọ́ ìbáwí ì mi ni, Ǹ bá ti tú ohun tí ó wà nínú ọkàn mi jáde fún yín kí n sì fi inú un mi hàn sí i yín
Bi e ba ti gbo ibawi i mi ni, N ba ti tu ohun ti o wa ninu okan mi jade fun yin ki n si fi inu un mi han si i yin
Tá a bá ń ṣe bẹ́ẹ̀ , Jèhófà máa rí sí i pé ọwọ́ wa tẹ àwọn nǹkan tá a ṣaláìní .
Ta a ba n se bee , Jehofa maa ri si i pe owo wa te awon nnkan ta a salaini .
Àmọ́ , Jésù ò rí wọn bí ìdíwọ́ .
Amo , Jesu o ri won bi idiwo .
Nígbà tó yá , àwọn ọmọ ẹ̀yìn Calvin gbé ọ̀kan lára ẹ̀kọ́ wọn tó ń fa àríyànjiyàn jù lọ jáde , ìyẹn àyànmọ́ .
Nigba to ya , awon omo eyin Calvin gbe okan lara eko won to n fa ariyanjiyan ju lo jade , iyen ayanmo .
Kí Nìdí Tí Ohun Tí Mátíù àti Lúùkù Sọ Nípa Ìgbà Tí Jésù Wà Ní Kékeré Fi Yàtọ̀ Síra ? Aug .
Ki Nidi Ti Ohun Ti Matiu ati Luuku So Nipa Igba Ti Jesu Wa Ni Kekere Fi Yato Sira ? Aug .
Ká tó lè “ sá fún àgbèrè , ” a gbọ́dọ̀ yẹra fún gbogbo ohun tó jẹ́ mọ́ ìwà àìmọ́ takọtabo àti ìwà àìníjàánu tó lè súnni dórí dídá ẹ̀ṣẹ̀ por·neiʹa tó burú jáì .
Ka to le “ sa fun agbere , ” a gbodo yera fun gbogbo ohun to je mo iwa aimo takotabo ati iwa ainijaanu to le sunni dori dida ese por·neiʹa to buru jai .
Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀
Jesu si kilo fun won gidigidi pe ki won ma se so ohun ti o ti sele
Ìran yìí ń tọ́ka sí Ìjọba Ọlọ́run , nígbà tí Jésù àtàwọn tó jíǹde látinú ayé á máa ṣàkóso , tí wọ́n á sì fòpin sí ìṣàkóso Sátánì .
Iran yii n toka si Ijoba Olorun , nigba ti Jesu atawon to jinde latinu aye a maa sakoso , ti won a si fopin si isakoso Satani .
Ó tiẹ̀ wó àga mọ́ akẹ́kọ̀ọ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ nígbà kan , ó sì fi pẹ́ńsù gún akẹ́kọ̀ọ́ mìíràn .
O tie wo aga mo akekoo elegbe re nigba kan , o si fi pensu gun akekoo miiran .
Yára láti ràn mí lọ́wọ́,, Olùgbàlà mi.
Yara lati ran mi lowo,, Olugbala mi.
Jerusalẹmu, Lẹ́yìn Ìṣubú Rẹ̀.
Jerusalemu, Leyin Isubu Re.
Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì tá a lò nínú ọkọ̀ ojú irin , a dé ìlú Asino ní àgbègbè Tomsk , wọ́n sì dà wá sílẹ̀ níbẹ̀ bí màlúù .
Leyin ose meji ta a lo ninu oko oju irin , a de ilu Asino ni agbegbe Tomsk , won si da wa sile nibe bi maluu .
Bí ọ̀gá ilé iṣẹ́ kan bá sì sọ fún ọ pé àwọn ò ní iṣẹ́ táwọn lè fún ọ ṣe , bi í léèrè bóyá ó mọ ibòmíì tó o lè wáṣẹ́ sí àtẹni tó o lè kàn sí .
Bi oga ile ise kan ba si so fun o pe awon o ni ise tawon le fun o se , bi i leere boya o mo ibomii to o le wase si ateni to o le kan si .
Lẹ́yìn náà , “ Bárákì sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀ kalẹ̀ láti orí Òkè Ńlá Tábórì pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ọkùnrin lẹ́yìn rẹ̀ . ” ​ — Àwọn Onídàájọ́ 4 : 14 .
Leyin naa , " Baraki si bere si so kale lati ori Oke Nla Tabori pelu egberun mewaa okunrin leyin re . " -- Awon Onidaajo 4 : 14 .
Kristi ti rà wá padà kúrò lọ́wọ́ ègún òfin, ẹni tí a fi ṣe ègún fún wa: nítorí tí a ti kọ ọ́ pé, “Ìfibú ni olúkúlùkù ẹni tí a fi kọ́ sórí igi.”
Kristi ti ra wa pada kuro lowo egun ofin, eni ti a fi se egun fun wa: nitori ti a ti ko o pe, "Ifibu ni olukuluku eni ti a fi ko sori igi."
Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi–Ìdílé Kohati.
Ise Awon Omo Lefi-Idile Kohati.
Nítorí náà , ní ẹ̀wádún tó kọjá , gbogbo Àkájọ Ìwé Òkun Òkú ló ti wà lárọ̀ọ́wọ́tó fún àyẹ̀wò .
Nitori naa , ni ewadun to koja , gbogbo Akajo Iwe Okun Oku lo ti wa laroowoto fun ayewo .
Ohun tó yẹ kó o fi sọ́kàn : Àkókò tá a wà yìí ló ṣe pàtàkì jù lọ pé káwọn òbí ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ láti “ kọ́ agbára ìwòye wọn ” kí wọ́n lè máa “ fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tí ó tọ́ àti ohun tí kò tọ́ . ” ​ — Hébérù 5 : 14 .
Ohun to ye ko o fi sokan : Akoko ta a wa yii lo se pataki ju lo pe kawon obi ran awon omo won lowo lati “ ko agbara iwoye won ” ki won le maa “ fi iyato saaarin ohun ti o to ati ohun ti ko to . ” ​ — Heberu 5 : 14 .
Bẹ́ẹ̀ ni , bá a ṣe ń ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ , ńṣe ni à ń “ làdí ” Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tá a sì “ ń fi ìtumọ̀ sí i ” bí wọ́n ti ṣe nígbà ayé Nehemáyà . — Neh .
Bee ni , ba a se n se Ikekoo Ile Iso losoose , nse ni a n " ladi " Oro Olorun ta a si " n fi itumo si i " bi won ti se nigba aye Nehemaya . -- Neh .
Nígbà míì sì rèé , gbogbo àwọn tí wọ́n jọ ń sọ èdè kan náà kì í ju àwọn tí wọ́n kàn jọ ń gbé ní àwọn abúlé kéékèèké mélòó kan lọ .
Nigba mii si ree , gbogbo awon ti won jo n so ede kan naa ki i ju awon ti won kan jo n gbe ni awon abule keekeeke meloo kan lo .
Ìwé Òwe 24 : 10 sọ pé : “ Ìwọ ha ti jẹ́ kí ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọ ní ọjọ́ wàhálà bí ?
Iwe Owe 24 : 10 so pe : “ Iwo ha ti je ki irewesi ba o ni ojo wahala bi ?
Nígbà tó o bá wà nínú ìpọ́njú , ìwọ́ náà lè lo ìdánúṣe láti yanjú ìṣòro rẹ .
Nigba to o ba wa ninu iponju , iwo naa le lo idanuse lati yanju isoro re .
( a ) Kí ni olórí ohun tó ń mú wa tọ́jú àwọn òbí wa àgbàlagbà ?
( a ) Ki ni olori ohun to n mu wa toju awon obi wa agbalagba ?
Nuuh àti (iran) 'Aad àti Fir'aona,
Nuuh ati (iran) 'Aad ati Fir'aona,
Nínú ọ̀rọ̀ yìí , àwọn òbí ẹ ló wà nípò àṣẹ .
Ninu oro yii , awon obi e lo wa nipo ase .
Kó o tó fẹsẹ̀ lé ọ̀nà kan , kọ́kọ́ bi ara rẹ pé , ‘ Kí ló máa jẹ́ ìgbẹ̀yìn rẹ̀ ? ’
Ko o to fese le ona kan , koko bi ara re pe , ' Ki lo maa je igbeyin re ? '