diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Wọn kò sì rántí Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn gbogbo tí ó wà ní gbogbo àyíká wọn.
Won ko si ranti Olorun won, eni ti o gba won kuro lowo awon ota won gbogbo ti o wa ni gbogbo ayika won.
Yíká ayé , ọrẹ àtinúwá ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń lò láti fi kọ́ àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba , Gbọ̀ngàn Àpéjọ , ẹ̀ka ọ́fíìsì àtàwọn ilé ìtẹ̀wé wọn , ọrẹ àtinúwá yìí náà ni wọ́n sì ń lò láti fi ṣèrànwọ́ fún àwọn tí àjálù dé bá .
Yika aye , ore atinuwa ni awon Elerii Jehofa n lo lati fi ko awon Gbongan Ijoba , Gbongan Apejo , eka ofiisi atawon ile itewe won , ore atinuwa yii naa ni won si n lo lati fi seranwo fun awon ti ajalu de ba .
Jóòbù kì í ṣe èèyànkéèyàn tàbí òǹrorò ẹ̀dá .
Joobu ki i se eeyankeeyan tabi onroro eda .
Ẹni tí ó ti búra fún ,tí ó sì ṣe ìlérí fún Alágbára Jakọbu pé.
Eni ti o ti bura fun ,ti o si se ileri fun Alagbara Jakobu pe.
Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ èyíkéyí nínú òkú ẹranko náà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, yóò sì di aláìmọ́ títí ìrọ̀lẹ́
Enikeni ti o ba je eyikeyi ninu oku eranko naa gbodo fo aso re, yoo si di alaimo titi irole
Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ sí Ìrònú Ẹni Tó Bá Ti Kú ?
Ki Lo Maa N Sele si Ironu Eni To Ba Ti Ku ?
Ẹ máa ronú nípa àwọn tó wà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín àti ohun tó máa mú kí wọ́n fẹ́ tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ yín .
E maa ronu nipa awon to wa ni ipinle iwaasu yin ati ohun to maa mu ki won fe teti si oro yin .
Èyí ni ohun tí Olúwa sọ
Eyi ni ohun ti Oluwa so
Ọmọ afẹ̀jẹ̀ ẹlẹ́jẹ̀ wẹ̀
Omo afeje eleje we
Ó mú kí àjọṣe rẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run túbọ̀ dán mọ́rán sí i .
O mu ki ajose re pelu Olorun tubo dan moran si i .
Bí àpẹẹrẹ , ọkùnrin kan tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ wá sọ́dọ̀ Jésù , ó sì bẹ̀ ẹ́ pé : “ Bí ìwọ bá sáà ti fẹ́ bẹ́ẹ̀ , ìwọ lè mú kí èmi mọ́ . ”
Bi apeere , okunrin kan to ni arun ete wa sodo Jesu , o si be e pe : " Bi iwo ba saa ti fe bee , iwo le mu ki emi mo . "
Tó bá rí bẹ́ẹ̀ , ẹ jẹ́ ká ‘ ra oògùn ojú lọ́dọ̀ Jésù ’ ká lè rí bó ti ṣe pàtàkì tó láti fi ìtara wá Ìjọba náà lákọ̀ọ́kọ́ . — Mátíù 6 : 33 .
To ba ri bee , e je ka ‘ ra oogun oju lodo Jesu ’ ka le ri bo ti se pataki to lati fi itara wa Ijoba naa lakooko . — Matiu 6 : 33 .
Àmọ́ , Isaac Comnenus ní kí wọ́n mú un , wọ́n jù ú sẹ́wọ̀n , wọ́n sì lé e lọ sí erékùṣù Imbros .
Amo , Isaac Comnenus ni ki won mu un , won ju u sewon , won si le e lo si erekusu Imbros .
“ Alátakò ” ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ náà , “ Sátánì . ”
“ Alatako ” ni itumo oro naa , “ Satani . ”
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24
APILEKO FUN IKEKOO 3 OJU IWE 20 si 24
Mo gbádùn oṣù yẹn gan - an débi pé lọ́dún 1996 , mo di aṣáájú - ọ̀nà déédéé , ìyẹn òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó ń lo àádọ́rùn - ún [ 90 ] wákàtí lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù lóṣooṣù .
Mo gbadun osu yen gan - an debi pe lodun 1996 , mo di asaaju - ona deedee , iyen ojise Olorun to n lo aadorun - un [ 90 ] wakati lenu ise iwaasu losoosu .
Òótọ́ ni pé kì í ṣe gbogbo ọkọ , aya , àwọn ọmọ , àwọn òbí tàbí àwọn mọ̀lẹ́bí tó jẹ́ aláìgbàgbọ́ ló máa ń wá sínú ìjọsìn tòótọ́ , kódà lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún tí ẹni tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí ti ń hùwà tó dáa , tó sì ti ń fi ọgbọ́n wàásù fún wọn .
Ooto ni pe ki i se gbogbo oko , aya , awon omo , awon obi tabi awon molebi to je alaigbagbo lo maa n wa sinu ijosin tooto , koda leyin opo odun ti eni to je Elerii ti n huwa to daa , to si ti n fi ogbon waasu fun won .
Èyí ló mú kí Pọ́ọ̀lù tún èrò pa tó sì kọ lẹ́tà tá a wá mọ̀ sí Kọ́ríńtì Kìíní .
Eyi lo mu ki Poolu tun ero pa to si ko leta ta a wa mo si Korinti Kiini .
Bí wọ́n bá tiẹ̀ ti gba kámú tẹ́lẹ̀ , ó máa ń mú kí wọ́n fẹ́ láti ṣe nǹkan kan kí wọ́n lè yanjú ìṣòro náà .
Bi won ba tie ti gba kamu tele , o maa n mu ki won fe lati se nnkan kan ki won le yanju isoro naa .
Ọré mi keji Abdullai Awòlúmátẹ̀€, ẹni tí orúkọ rẹ̀ n pòwe kì í
Ore mi keji Abdullai Awolumate€, eni ti oruko re n powe ki i
Ìjọba ọ̀run tí Ẹlẹ́dàá ìran ènìyàn , Jèhófà Ọlọ́run dá sílẹ̀ , èyí tí Jésù Kristi yòó máa ṣàkóso bí Ọba rẹ̀ ni yóò mú àyípadà yìí wá .
Ijoba orun ti Eledaa iran eniyan , Jehofa Olorun da sile , eyi ti Jesu Kristi yoo maa sakoso bi Oba re ni yoo mu ayipada yii wa .
nínú rẹ̀ àti pé kí ọkàn wa lẹ̀ balẹ̀, kí
ninu re ati pe ki okan wa le bale, ki
Ẹ máa kíyèsi àṣẹ mi, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́: Èmi ni tí ó sọ yín di mímọ́.
E maa kiyesi ase mi, ki e si maa pa won mo: Emi ni ti o so yin di mimo.
Lọ́dún 1823 , ṣàdédé ni akọ̀wé kan rí ìwé gbajúmọ̀ òǹkọ̀wé ewì yìí , níbi tí wọ́n fi bébà wé e pa mọ́ sí .
Lodun 1823 , sadede ni akowe kan ri iwe gbajumo onkowe ewi yii , nibi ti won fi beba we e pa mo si .
Òpìtàn Carolly Erickson ṣàpèjúwe bí wọ́n ṣe ń sun wọ́n , ó wí pé : “ Lọ́pọ̀ ìgbà , igi tútù ni wọ́n fi máa ń dá iná náà , tàbí kí wọ́n lo koríko tútù tí kò ní tètè jó .
Opitan Carolly Erickson sapejuwe bi won se n sun won , o wi pe : " Lopo igba , igi tutu ni won fi maa n da ina naa , tabi ki won lo koriko tutu ti ko ni tete jo .
( Wo ìpínrọ̀ 17 )
( Wo ipinro 17 )
Lákọ̀ọ́kọ́ ná , Ọlọ́run sọ fún wa léraléra pé òun fẹ́ ràn wá lọ́wọ́ .
Lakooko na , Olorun so fun wa leralera pe oun fe ran wa lowo .
Àwọn ọ̀rọ̀ kan wà tí àwọn ènìyàn sọ ní orú yìí tí ó yẹ kí á ṣe àkíyèsí.
Awon oro kan wa ti awon eniyan so ni oru yii ti o ye ki a se akiyesi.
Bí ẹnikẹ́ni bá lóun gbójú gbóyà tó lọ kọlu àwọn yòókù tó máa di ara Ìjọba náà , ńṣe lonítọ̀hún ń fẹsẹ̀ wọnsẹ̀ pẹ̀lú Ìjọba Ọlọ́run . — Ìṣípayá 12 : 17 .
Bi enikeni ba loun gboju gboya to lo kolu awon yooku to maa di ara Ijoba naa , nse lonitohun n fese wonse pelu Ijoba Olorun . -- Isipaya 12 : 17 .
Ní àkókò yẹn , ó ṣeé ṣe kí inú rẹ dùn pé bàbá ni ọ́ .
Ni akoko yen , o see se ki inu re dun pe baba ni o .
Oníbàtá kì í wọ mọ́ṣáláṣí kó ní “Lèmámù ńkọ́?”
Onibata ki i wo mosalasi ko ni “Lemamu nko?”
Lójú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà , kì í ṣe torí pé wọ́n kàn fẹ́ tan ẹ̀sìn kálẹ̀ ni wọ́n ṣe ń lọ láti ẹnu ọ̀nà dé ẹnu ọ̀nà láti yíni lọ́kàn pa dà , àmọ́ ṣe ni wọ́n gbà pe iṣẹ́ yẹn jẹ́ ọ̀nà pàtàkì téèyàn gbà ń fi hàn pé òun ní ìgbàgbọ́ . ”
Loju awon Elerii Jehofa , ki i se tori pe won kan fe tan esin kale ni won se n lo lati enu ona de enu ona lati yini lokan pa da , amo se ni won gba pe ise yen je ona pataki teeyan gba n fi han pe oun ni igbagbo . "
Inú mi ń dùn láti máa ṣètìlẹ́yìn fún ọkọ mi bó ṣe ń ṣèrànwọ́ láti bójú tó ìjọ tí à ń dara pọ̀ mọ́ .
Inu mi n dun lati maa setileyin fun oko mi bo se n seranwo lati boju to ijo ti a n dara po mo .
Nítorí náà , a ń fi ìdánilójú sọ pé : “ Bí Ọlọ́run bá wà fún wa , ta ni yóò wà lòdì sí wa ? ” — Róòmù 8 : 31 .
Nitori naa , a n fi idaniloju so pe : “ Bi Olorun ba wa fun wa , ta ni yoo wa lodi si wa ? ” — Roomu 8 : 31 .
Fífọ́ ejò ní orí kan jíju Sátánì sínú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀ nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìjọba Kristi .
Fifo ejo ni ori kan jiju Satani sinu ogbun ainisale nigba Egberun Odun Ijoba Kristi .
Mi ò jẹ́ kóyán ẹ̀ kéré , ọ̀pọ̀ ìgbà ni mo máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà lóòjọ́ pó jẹ́ kí n bí ọmọ náà . ”
Mi o je koyan e kere , opo igba ni mo maa n dupe lowo Jehofa loojo po je ki n bi omo naa . ”
Gẹ́gẹ́ bí ohun tí Bíbélì sọ , báwo ni Jèhófà ṣe pèsè ìrànwọ́ nípasẹ̀ àwọn onígbàgbọ́ ẹlẹgbẹ́ ẹni ?
Gege bi ohun ti Bibeli so , bawo ni Jehofa se pese iranwo nipase awon onigbagbo elegbe eni ?
Tá a bá fẹ́ wà lára “ agbo kan , ” tá a sì fẹ́ máa tẹ̀ lé “ olùṣọ́ àgùntàn kan , ” àfi ká máa wá sípàdé déédéé .
Ta a ba fe wa lara " agbo kan , " ta a si fe maa te le " oluso aguntan kan , " afi ka maa wa sipade deedee .
Ọlọ́rùn títóbi àti alágbára, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ
Olorun titobi ati alagbara, Oluwa awon omo-ogun ni oruko re
Ògo OLUWA gbéra kúrò láàrin ìlú náà, ó sì dúró sórí òkè tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn ìlú náà.
Ogo OLUWA gbera kuro laarin ilu naa, o si duro sori oke ti o wa ni apa iha ila oorun ilu naa.
Nígbà yẹn , Ábúráhámù kò lóye ohun tí májẹ̀mú náà máa túmọ̀ sí fún aráyé délẹ̀délẹ̀ .
Nigba yen , Aburahamu ko loye ohun ti majemu naa maa tumo si fun araye deledele .
Ó ṣe tán , àwa Kristẹni gbọ́dọ̀ jẹ́ olóòótọ́ .
O se tan , awa Kristeni gbodo je oloooto .
Lipoftsoff túmọ̀ .
Lipoftsoff tumo .
Kódà , láàárín àwọn Kristẹni tó ń gbé lápá ibì kan náà , ohun tó máa ń gbádùn mọ́ ẹnì kan ( bóyá kíka ìwé aládùn ) , lè máa sú ẹlòmíì ; ohun tó ń tu ẹnì kan lára ( bóyá kó máa gun kẹ̀kẹ́ najú káàkiri ) , lè jẹ́ ohun tó máa ń mú kó rẹ ẹlòmíì .
Koda , laaarin awon Kristeni to n gbe lapa ibi kan naa , ohun to maa n gbadun mo eni kan ( boya kika iwe aladun ) , le maa su elomii ; ohun to n tu eni kan lara ( boya ko maa gun keke naju kaakiri ) , le je ohun to maa n mu ko re elomii .
O lọ si Ile-ẹkọ Gẹẹsi Geneva ati lẹhinna Ile-ẹkọ Alakọbẹrẹ Home Science, Ikoyi, fun eto-ẹkọ ti o kọkọ.
O lo si Ile-eko Geesi Geneva ati lehinna Ile-eko Alakobere Home Science, Ikoyi, fun eto-eko ti o koko.
Ó wá pọn dandan káwa èèyàn ẹlẹ́ṣẹ̀ rí ọ̀nà láti pa dà bá Jèhófà rẹ́ .
O wa pon dandan kawa eeyan elese ri ona lati pa da ba Jehofa re .
Ọ̀ṣọ́ọ́rọ́ obìnrin kan wà ní Íńdíà tó nílò ìtùnú lójú méjèèjì .
Osooro obinrin kan wa ni India to nilo itunu loju mejeeji .
aṣíiwájú wọn ṣe n gbààyẹ̀. Báyìí
asiiwaju won se n gbaaye. Bayii
Ronald Morrish , tó jẹ́ ògbógi nínú ọ̀ràn ìhùwà , sọ pé : “ Bí àwọn ọmọ bá mọ ààlà wọn , ó máa ń jẹ́ kí wọ́n rí ìdí tó fi yẹ kí wọ́n mọ ohun tí wọ́n ní láti retí àti ààbò wọn — tí yóò wá ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ní iyì tó túbọ̀ pọ̀ .
Ronald Morrish , to je ogbogi ninu oran ihuwa , so pe : " Bi awon omo ba mo aala won , o maa n je ki won ri idi to fi ye ki won mo ohun ti won ni lati reti ati aabo won -- ti yoo wa ran won lowo lati ni iyi to tubo po .
7. Àti pé báyìí ni Olúwa rẹ̀ yôò
7. Ati pe bayii ni Oluwa re yoo
Wọ́n fi bíbá àwọn aládùúgbò wọn sọ̀rọ̀ lọ́nà tó yááyì kún iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn .
Won fi biba awon aladuugbo won soro lona to yaayi kun ise ojise won .
( b ) Kí ló fi hàn pé Ámósì kì í ṣe púrúǹtù ?
( b ) Ki lo fi han pe Amosi ki i se puruntu ?
A KÒ gbọ́dọ̀ jiyàn rẹ̀ pé iṣẹ́ tí wọ́n pè ní “ iṣẹ́ tó dára jù lọ ” yìí ń kojú onírúurú ìṣòro .
A KO gbodo jiyan re pe ise ti won pe ni “ ise to dara ju lo ” yii n koju oniruuru isoro .
Ní oṣù karùn-ún ọdún keje ọba yìí ni Esra dé sí Jerusalẹmu.
Ni osu karun-un odun keje oba yii ni Esra de si Jerusalemu.
49. Àwa sì ti sọ Ìwé náà tí òô kún
49. Awa si ti so Iwe naa ti oo kun
Ní wákàtí kan náà, díẹ̀ nínú àwọn Farisi tọ̀ ọ́ wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Jáde, kí ìwọ sì lọ kúrò níhìn-ín yìí: nítorí Herodu ń fẹ́ pa ọ́.”
Ni wakati kan naa, die ninu awon Farisi to o wa, won si wi fun un pe, "Jade, ki iwo si lo kuro nihin-in yii: nitori Herodu n fe pa o."
Korobá kan tí kò ní ìdérí ni ilé ìgbọ̀nsẹ̀ tó wà níbi tí wọ́n tì mí mọ́ .
Koroba kan ti ko ni ideri ni ile igbonse to wa nibi ti won ti mi mo .
Kíyèsí i, èmí ti dúró de ọ̀rọ̀ yín
Kiyesi i, emi ti duro de oro yin
Níkẹyìn , a dé New York , níbi tá a ti ṣe àpéjọ náà .
Nikeyin , a de New York , nibi ta a ti se apejo naa .
elúsáì
elusai
Ṣùgbọ́n, èmi yóò mú Israẹlipadà wá pápá oko tútù rẹ̀òun yóò sì máa bọ́ ara rẹ̀ lórí Karmeli àti Baṣani,a ó sì tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn ní òkèEfraimu àti ní Gileadi
Sugbon, emi yoo mu Israelipada wa papa oko tutu reoun yoo si maa bo ara re lori Karmeli ati Basani,a o si te okan re lorun ni okeEfraimu ati ni Gileadi
Ṣe ni wọ́n gbà pé ó máa bu Ọlọ́run kù tí a bá sọ pé ó jẹ́ ọkàn , torí ọ̀rọ̀ yẹn ni Bíbélì máa ń lò fún àwọn ẹ̀dá abẹ̀mí inú ayé .
Se ni won gba pe o maa bu Olorun ku ti a ba so pe o je okan , tori oro yen ni Bibeli maa n lo fun awon eda abemi inu aye .
Wọ́n torí ajá ńlóṣòó lọ fowó rọ̀bọ.
Won tori aja nlosoo lo fowo robo.
Nígbà tí òpìtàn Augustus Neander ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn Kristẹni ọ̀rúndún kìíní , ohun tó kọ sínú ìwé rẹ̀ tó dá lórí ìsìn Kristẹni ni pé : “ Kìkì àwọn tó dàgbà ló máa ń ṣe ìrìbọmi níbẹ̀rẹ̀ , nítorí pé àwọn èèyàn gbà pé kò sẹ́ni tó lè ṣèrìbọmi láìní ìgbàgbọ́ . ” — Ìwé General History of the Christian Religion and Church .
Nigba ti opitan Augustus Neander n soro nipa awon Kristeni orundun kiini , ohun to ko sinu iwe re to da lori isin Kristeni ni pe : “ Kiki awon to dagba lo maa n se iribomi nibere , nitori pe awon eeyan gba pe ko seni to le seribomi laini igbagbo . ” — Iwe General History of the Christian Religion and Church .
Nígbà tó lọ lo àkókò ìsinmi lórílẹ̀ - èdè Cambodia , ọmọbìnrin kan wá tọrọ owó lọ́wọ́ rẹ̀ nígbà tó ń jẹun lọ́wọ́ nílé oúnjẹ kan nílùú Phnom Penh .
Nigba to lo lo akoko isinmi lorile - ede Cambodia , omobinrin kan wa toro owo lowo re nigba to n jeun lowo nile ounje kan niluu Phnom Penh .
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
Ibeere Lati Owo Awon Onkawe
Máa gbẹ́sẹ̀ lọ́kọ̀ọ̀kan , ní ṣísẹ̀ - n - tẹ̀lé , láìkánjú .
Maa gbese lokookan , ni sise - n - tele , laikanju .
Ó wá fi kún un pé : “ Dẹ etí rẹ sí ìfòyemọ̀ mi , kí o bàa lè ṣọ́ agbára láti ronú ; kí ètè tìrẹ sì fi ìṣọ́ ṣọ́ ìmọ̀ . ” — Òwe 5 : 1 , 2 .
O wa fi kun un pe : " De eti re si ifoyemo mi , ki o baa le so agbara lati ronu ; ki ete tire si fi iso so imo . " -- Owe 5 : 1 , 2 .
Lóòótọ́ , iṣẹ́ àwọn alàgbà pọ̀ gan - an .
Loooto , ise awon alagba po gan - an .
Kí ló ti jẹ́ àbájáde ìbínú òdì tó ń tàn kálẹ̀ yìí ?
Ki lo ti je abajade ibinu odi to n tan kale yii ?
Ilu naa ni awọn cul-de-sacs tabi awọn pipade eyiti o jẹ orukọ ni ọna kika alfabeti kan.
Ilu naa ni awon cul-de-sacs tabi awon pipade eyiti o je oruko ni ona kika alfabeti kan.
Ǹjẹ́ O Mọ Ṣáfánì àti Ìdílé Rẹ̀ ?
Nje O Mo Safani ati Idile Re ?
Àníyàn tí ọba yìí ń ṣe nípa bí ẹ̀sìn Pùròtẹ́sítáǹtì ṣe tàn kálẹ̀ ló mú kó ṣèwádìí nípa àwọn tí wọ́n pè ní aládàámọ̀ nínú ìjọba rẹ̀ .
Aniyan ti oba yii n se nipa bi esin Purotesitanti se tan kale lo mu ko sewadii nipa awon ti won pe ni aladaamo ninu ijoba re .
Ó jẹ́ pé lítíréṣọ̀ ni ọ̀rọ̀ tàbí èdè ọgbọ́n tí a fi ohun gbé jáde ni àwùjọ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ kí ó tó di kíkọ́ sílẹ̀ nípa ìlànà mọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà ní àwùjọ alákọ̀wé Èrò yìí tẹ̀síwàjú nígbà tí Babalọlá sọ pé lítíréṣọ̀ ni ìlànà tí à ń gbà sọ fún ayé gbọ́ ohun tí ó jẹ ni lọ́kàn nípa àyíká Èyí tí a gbé kalẹ̀ lọ́nà tààrà tàbí lọ́nà àlùmọ̀kọ́rọ́yí lọ́pọ̀ ìgbà láì dárúkọ pàtó àwọn ẹní ti ọ̀rọ̀ kàn ganan Ṣùgbọ́n tí àṣàyàn ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ pẹ̀lú ohun tó fẹ́wa fún ohun tí à ń sọ náà ń ṣáábà jẹ ẹní tí ń ṣe àgbékalẹ̀ lógún
O je pe litireso ni oro tabi ede ogbon ti a fi ohun gbe jade ni awujo soro soro ki o to di kiko sile nipa ilana mookomooka ni awujo alakowe Ero yii tesiwaju nigba ti Babalola so pe litireso ni ilana ti a n gba so fun aye gbo ohun ti o je ni lokan nipa ayika Eyi ti a gbe kale lona taara tabi lona alumokoroyi lopo igba lai daruko pato awon eni ti oro kan ganan Sugbon ti asayan oro ijinle pelu ohun to fewa fun ohun ti a n so naa n saaba je eni ti n se agbekale logun
bátànìi
batanii
Ṣugbọn mo ní nǹkan wí sí ọ. O ti kọ ìfẹ́ tí o ní nígbà tí o kọ́kọ́ gbàgbọ́ sílẹ̀.
Sugbon mo ni nnkan wi si o. O ti ko ife ti o ni nigba ti o koko gbagbo sile.
ṣe gbàgbé ìpin rẹ layé yìí, kí o sì
se gbagbe ipin re laye yii, ki o si
Àwa Kristẹni ‘ ní gídígbò kan lòdì sí àwọn agbo ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú ’
Awa Kristeni ‘ ni gidigbo kan lodi si awon agbo omo ogun emi buruku ’
Town in Lagos State, NigeriaÀdàkọ:SHORTDESC:Town in Lagos State, Nigeria Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT)
Town in Lagos State, NigeriaAdako:SHORTDESC:Town in Lagos State, Nigeria Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT)
Wọn ò di ojúlùmọ̀ ọ̀rọ̀ náà nípa jíjẹ́ kó máa darí wọn láti ṣe ìpinnu tó mọ́gbọ́n dáni nígbèésí ayé wọn .
Won o di ojulumo oro naa nipa jije ko maa dari won lati se ipinnu to mogbon dani nigbeesi aye won .
1 , 2 . ( a ) Àǹfààní wo ni Jésù gbé lé àpọ́sítélì Pétérù lọ́wọ́ , kí ló sì fi hàn pé kò sóun tó burú nínú bí Jésù ṣe fọkàn tán Pétérù ?
1 , 2 . ( a ) Anfaani wo ni Jesu gbe le apositeli Peteru lowo , ki lo si fi han pe ko soun to buru ninu bi Jesu se fokan tan Peteru ?
Bẹ́ẹ̀ sì rèé , ará Gálílì ni àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù tó ń bá wọn sọ̀rọ̀ .
Bee si ree , ara Galili ni awon omo eyin Jesu to n ba won soro .
Àwọn Kristẹni pàápàá ka bíbọ̀wọ̀ fún àwọn òbí àti nínífẹ̀ẹ́ wọn sí ohun pàtàkì .
Awon Kristeni paapaa ka bibowo fun awon obi ati ninifee won si ohun pataki .
Ohun tí àwọn tó gbé fíìmù yìí jáde ṣe ni pé wọ́n gbé kámẹ́rà aláfọwọ́yí kan sí iwájú ọkọ̀ kan tó ń rìn lára okùn irin tí wọ́n ta sára àwọn òpó gíga .
Ohun ti awon to gbe fiimu yii jade se ni pe won gbe kamera alafowoyi kan si iwaju oko kan to n rin lara okun irin ti won ta sara awon opo giga .
( b ) Báwo làwọn “ àgùntàn mìíràn ” ṣe ń ran àwọn ẹni àmì òróró yìí lọ́wọ́ ?
( b ) Bawo lawon “ aguntan miiran ” se n ran awon eni ami ororo yii lowo ?
Lára ohun tí Ọlọ́run ń pèsè fún wa ni “ ìtùnú ẹ̀mí mímọ́ . ”
Lara ohun ti Olorun n pese fun wa ni " itunu emi mimo . "
Àbí ẹ ò rí i pé Jèhófà fẹ́ràn láti máa dá àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ !
Abi e o ri i pe Jehofa feran lati maa da awon eeyan re lekoo !
Bóyá la fi rí ẹnì kan tí kò da omi lójú nínú wọn .
Boya la fi ri eni kan ti ko da omi loju ninu won .
Tún gbìyànjú láti wo ọ̀ràn náà bí Jehófà ṣe wò ó .
Tun gbiyanju lati wo oran naa bi Jehofa se wo o .
Ọkọ kan tó ń jẹ́ Carlos sọ pé : “ Inú àwa ọkùnrin máa ń dùn tá a bá rí i pé a lè bójú tó ìdílé wa , ká sì yanjú ìṣòro . ”
Oko kan to n je Carlos so pe : “ Inu awa okunrin maa n dun ta a ba ri i pe a le boju to idile wa , ka si yanju isoro . ”
Báwo lo ṣe máa kọ́ ọmọ rẹ tí kò tíì pé ogún ọdún nípa irú ìbálòpọ̀ tí ó tọ́ ?
Bawo lo se maa ko omo re ti ko tii pe ogun odun nipa iru ibalopo ti o to ?
“Ọmọ ènìyàn, àwọn arákùnrin rẹ, àní àwọn ará rẹ, àwọn ọkùnrin nínú ìbátan rẹ, àti gbogbo ilé Israẹli pátápátá, ni àwọn ará Jerusalẹmu ti wí fún pé, ‘Ẹ jìnnà sí , àwa ni a fi ilẹ̀ yìí fún yín ní ìní.’
“Omo eniyan, awon arakunrin re, ani awon ara re, awon okunrin ninu ibatan re, ati gbogbo ile Israeli patapata, ni awon ara Jerusalemu ti wi fun pe, ‘E jinna si , awa ni a fi ile yii fun yin ni ini.’
Peteru sì wí pé, “Nítorí a ti kọ ọ́ nípa rẹ̀ nínú Ìwé Saamu pé,“ ‘Jẹ́ ki ibùgbé rẹ̀ di ahoro,kí ẹnikẹ́ni má ṣe gbé inú rẹ̀,’àti,“ ‘Ipò rẹ̀ ni kí ẹlòmíràn kí ó gbà.’
Peteru si wi pe, "Nitori a ti ko o nipa re ninu Iwe Saamu pe," 'Je ki ibugbe re di ahoro,ki enikeni ma se gbe inu re,'ati," 'Ipo re ni ki elomiran ki o gba.'
Gbogbo ìgbà tó bá lọ kọ́ obìnrin náà lẹ́kọ̀ọ́ ló máa ń rí ọmọ náà tó ń fi ìbọn oníke kékeré kan ṣeré , ohun ìṣeré kan ṣoṣo tó sì ní nìyẹn .
Gbogbo igba to ba lo ko obinrin naa lekoo lo maa n ri omo naa to n fi ibon onike kekere kan sere , ohun isere kan soso to si ni niyen .
Nítorí náà, ẹ gbé àánú wọ̀ bí ẹ̀wù, ati inú rere, ìrẹ̀lẹ̀, ìwà pẹ̀lẹ́ ati sùúrù, bí ó ti yẹ àwọn ẹni tí Ọlọrun yàn, tí wọ́n sì jẹ́ eniyan Ọlọrun ati àyànfẹ́ rẹ̀.
Nitori naa, e gbe aanu wo bi ewu, ati inu rere, irele, iwa pele ati suuru, bi o ti ye awon eni ti Olorun yan, ti won si je eniyan Olorun ati ayanfe re.
Wọ́n ń fi sọ́kàn pé àwọn èèyàn lẹ́tọ̀ọ́ láti ṣe ẹ̀sìn tó bá wù wọ́n .
Won n fi sokan pe awon eeyan letoo lati se esin to ba wu won .
Nítorí náà , á dáa kó o wáyè láti kíyè sí ẹnì kan dáadáa kó o lè rí i bóyá ìwà rẹ̀ bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mu .
Nitori naa , a daa ko o waye lati kiye si eni kan daadaa ko o le ri i boya iwa re ba oro re mu .
Òun sì máa fì yan àwọn tí ô bá wù
Oun si maa fi yan awon ti o ba wu
Àmọ́ ní báyìí , a ti rí i pé kò sí bí àwa nìkan ṣe lè máa dá ṣe gbogbo nǹkan .
Amo ni bayii , a ti ri i pe ko si bi awa nikan se le maa da se gbogbo nnkan .
Ó dájú háún pé Jèhófà ló ń darí wọn .
O daju haun pe Jehofa lo n dari won .