diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Torí pé ìwọ náà lè la òpin tó ń bọ̀ já !
Tori pe iwo naa le la opin to n bo ja !
Ṣé èyí lè rí bẹ́ẹ̀ bí kì í bá ṣe pé Ọlọ́run ti jí Jésù dìde ?
Se eyi le ri bee bi ki i ba se pe Olorun ti ji Jesu dide ?
Pọ́ọ̀lù sọ pé ohun tó fà á ni pé : Wọ́n ní ẹ̀rí ọkàn . — Ka Róòmù 2 : 14 , 15 .
Poolu so pe ohun to fa a ni pe : Won ni eri okan . -- Ka Roomu 2 : 14 , 15 .
Nítorí ní ọjọ́ méje sí ìhín, èmi yóò rọ òjò sórí ilẹ̀ fún ogójì ọ̀sán àti ogójì òru, èmi yóò sì pa gbogbo ohun alààyè tí mo ti dá run kúrò lórí ilẹ̀.”
Nitori ni ojo meje si ihin, emi yoo ro ojo sori ile fun ogoji osan ati ogoji oru, emi yoo si pa gbogbo ohun alaaye ti mo ti da run kuro lori ile."
Ṣùgbọ́n ǹjẹ́ o mọ ohun tí Ìjọba Ọlọ́run jẹ́ àti ohun tí yóò ṣe fún aráyé ?
Sugbon nje o mo ohun ti Ijoba Olorun je ati ohun ti yoo se fun araye ?
Federico Mayor , olùdarí àgbà fún àjọ UNESCO tẹ́lẹ̀ , fi taratara rawọ́ ẹ̀bẹ̀ pé àkókò ti tó “ láti dá àjọ kan sílẹ̀ fún ètò àlàáfíà àti àìsí ìwà ipá kárí ayé . ”
Federico Mayor , oludari agba fun ajo UNESCO tele , fi taratara rawo ebe pe akoko ti to " lati da ajo kan sile fun eto alaafia ati aisi iwa ipa kari aye . "
Tún gbé ìṣẹ̀lẹ̀ kan yẹ̀ wò , nípa Jáírù tó jẹ́ alága sínágọ́gù ní Kápánáúmù .
Tun gbe isele kan ye wo , nipa Jairu to je alaga sinagogu ni Kapanaumu .
Èmi yóò dà bí ìrì sí Ísírẹ́lì .
Emi yoo da bi iri si Isireli .
Ìwé gbédègbẹ́yọ̀ The World Book Encyclopedia sọ pé iṣẹ́ ìyanu jẹ́ “ ìṣẹ̀lẹ̀ kan tí a kò lè fi ìlànà bí àwọn nǹkan ṣe máa ń ṣẹlẹ̀ látọjọ́ táláyé ti dáyé ṣàlàyé rẹ̀ . ”
Iwe gbedegbeyo The World Book Encyclopedia so pe ise iyanu je " isele kan ti a ko le fi ilana bi awon nnkan se maa n sele latojo talaye ti daye salaye re . "
Tí a bá ti wàásù ìhìn rere náà dáadáa kárí ayé , lẹ́yìn náà ni Ìjọba Ọlọ́run máa mú ayé burúkú yìí lọ sópin .
Ti a ba ti waasu ihin rere naa daadaa kari aye , leyin naa ni Ijoba Olorun maa mu aye buruku yii lo sopin .
Tó o bá ń ti kékeré lo “ agbára ìmọnúúrò ” rẹ , wàá lè dáhùn táwọn ojúgbà rẹ bá bi ẹ́ láwọn ìbéèrè bíi : ‘ Kí ló mú kó dá ẹ lójú pé Ọlọ́run wà ní ti gidi ?
To o ba n ti kekere lo " agbara imonuuro " re , waa le dahun tawon ojugba re ba bi e lawon ibeere bii : ' Ki lo mu ko da e loju pe Olorun wa ni ti gidi ?
Ó sì ṣe tí èmi, Nífáì, wí fún
O si se ti emi, Nifai, wi fun
Nítorí a ti gbọ́ bí OLUWA ti mú kí Òkun Pupa gbẹ níwájú yín nígbà tí ẹ jáde ní Ijipti, a sì ti gbọ́ ohun tí ẹ ṣe sí Sihoni ati Ogu, àwọn ọba ará Amori mejeeji tí wọ́n wà ní òkè odò Jọdani, bí ẹ ṣe pa wọ́n run patapata.
Nitori a ti gbo bi OLUWA ti mu ki Okun Pupa gbe niwaju yin nigba ti e jade ni Ijipti, a si ti gbo ohun ti e se si Sihoni ati Ogu, awon oba ara Amori mejeeji ti won wa ni oke odo Jodani, bi e se pa won run patapata.
mélòómélòó ni a ó lọ́ àwọn wọ̀nyí, tí í ṣe ẹ̀ka-ìyẹ́ka sára igi ólífì wọn
meloomeloo ni a o lo awon wonyi, ti i se eka-iyeka sara igi olifi won
Wọ́n dé Jẹ́ríkò, bí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ àti ọ̀pọ̀ ènìyàn ti fẹ́ kúrò ní ìlú Jẹ́ríkò, ọkùnrin afọ́jú kan, Bátíméù, ọmọ Tíméù jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà ó ń sagbe
Won de Jeriko, bi Jesu ati awon omo-eyin re ati opo eniyan ti fe kuro ni ilu Jeriko, okunrin afoju kan, Batimeu, omo Timeu jokoo legbee ona o n sagbe
Bí wọ́n bá ká ẹran ọ̀sìn tí olè jí gbé mọ́ ọn lọ́wọ́ láàyè, kì báà ṣe akọ mààlúù, tabi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, tabi aguntan; ìlọ́po meji ni yóo fi san pada.
Bi won ba ka eran osin ti ole ji gbe mo on lowo laaye, ki baa se ako maaluu, tabi ketekete, tabi aguntan; ilopo meji ni yoo fi san pada.
Ohun tó bá wà lọ́kàn wa nígbà táwọn èèyàn bá gbóríyìn fún wa ló máa sọ irú ògo tàbí ọlá tá à ń wá . — Òwe 27 : 21 .
Ohun to ba wa lokan wa nigba tawon eeyan ba gboriyin fun wa lo maa so iru ogo tabi ola ta a n wa . -- Owe 27 : 21 .
ẹ̀kọ́ ṣékóndììrì onípele kéje dé
eko sekondiiri onipele keje de
65.. 'Àti pé kí o máa tan ẹnikéni
65.. 'Ati pe ki o maa tan enikeni
Bí Ẹni tí ó ní agbára ńlá , òun yóò gbà là .
Bi Eni ti o ni agbara nla , oun yoo gba la .
Bákan náà ni ìbú ati òòró rẹ̀ yóo rí, ìṣẹ́po meji ni yóo jẹ́, ìbú ati òòró rẹ̀ yóo sì jẹ́ ìká kọ̀ọ̀kan.
Bakan naa ni ibu ati ooro re yoo ri, isepo meji ni yoo je, ibu ati ooro re yoo si je ika kookan.
( b ) Ẹ̀bùn tó ti ọ̀dọ̀ Jèhófà wá wo ló mú kó rọrùn fún wa láti sìn ín ?
( b ) Ebun to ti odo Jehofa wa wo lo mu ko rorun fun wa lati sin in ?
Igi àjàrà a wọn wá láti igi àjàrà Sodomuàti ti ìgbẹ́ ẹ Gomorra.Èso àjàrà wọn kún fún oró,Ìdì wọn korò.
Igi ajara a won wa lati igi ajara Sodomuati ti igbe e Gomorra.Eso ajara won kun fun oro,Idi won koro.
nípa bẹ́ẹ̀ àwítúnwí odindi isọ
nipa bee awitunwi odindi iso
Ní September , ọdún 2012 , ilé iṣẹ́ ìròyìn BBC sọ pé : “ Ohun tó lé ní ìdá mẹ́jọ nínú mẹ́wàá òkun táwọn èèyàn ti ń pẹja ni wọ́n ti fẹ́rẹ̀ẹ́ pa ẹja inú rẹ̀ tán , wọn ò sì tíì dẹ̀yìn lẹ́yìn àwọn òkun náà . ”
Ni September , odun 2012 , ile ise iroyin BBC so pe : " Ohun to le ni ida mejo ninu mewaa okun tawon eeyan ti n peja ni won ti feree pa eja inu re tan , won o si tii deyin leyin awon okun naa . "
Àti nínú àwọn ọmọ àwọn àlùfáà:Àwọn ọmọ:Hobaiah, Hakosi àti Barsillai (ọkùnrin tí ó fẹ́ ọmọbìnrin Barsillai ará Gileadi a sì ń fi orúkọ náà pè é).
Ati ninu awon omo awon alufaa:Awon omo:Hobaiah, Hakosi ati Barsillai (okunrin ti o fe omobinrin Barsillai ara Gileadi a si n fi oruko naa pe e).
( b ) Àwọn ìbéèrè wo ló yẹ ká fi wádìí ara wa wò tó bá kan ọ̀ràn àdúrà gbígbà ?
( b ) Awon ibeere wo lo ye ka fi wadii ara wa wo to ba kan oran adura gbigba ?
sì gba ìyàwó rẹ̀ náà
si gba iyawo re naa
Ohun tó ṣe yìí sì múnú àwọn áńgẹ́lì olóòótọ́ tó wà lọ́run dùn .
Ohun to se yii si munu awon angeli oloooto to wa lorun dun .
gbòǹgbò ẹgbẹ́ ahmaddiya tún pínyà
gbongbo egbe ahmaddiya tun pinya
Láàárín sáà kúkúrú , ìyẹn ti tó láti mú kí ọ̀pọ̀ jù lọ ènìyàn ṣàìsàn .
Laaarin saa kukuru , iyen ti to lati mu ki opo ju lo eniyan saisan .
Torí náà , ó bọ́gbọ́n mu pé kó o yàgò fún wíwo àwọn fíìmù , kíkàwé àti gbígbọ́ àwọn orin tó ń mú ọkàn ẹni fà sí ìbálòpọ̀ .
Tori naa , o bogbon mu pe ko o yago fun wiwo awon fiimu , kikawe ati gbigbo awon orin to n mu okan eni fa si ibalopo .
Bí ó bá jẹ́ ìgbà kan, tí èmi kéde kí orílẹ̀-èdè tàbí ìjọba kan di fífà tu láti dojúdé àti láti parun.
Bi o ba je igba kan, ti emi kede ki orile-ede tabi ijoba kan di fifa tu lati dojude ati lati parun.
Ìwọ̀nyí jẹ́ àkókò tá a lè fún àwọn tára wọn ò le lókun , tá a lè sọ̀rọ̀ ìtùnú fáwọn tó sorí kọ́ , ká sì tu àwọn tó ń ṣàìsàn nínú .
Iwonyi je akoko ta a le fun awon tara won o le lokun , ta a le soro itunu fawon to sori ko , ka si tu awon to n saisan ninu .
Látìgbà tá a ti ṣègbéyàwó ní January 27 , 1951 ni Emily ti jẹ́ alábàáṣiṣẹ́ tó ṣeé gbára lé àti alábàákẹ́gbẹ́ tó ń fún mi ní ìṣírí .
Latigba ta a ti segbeyawo ni January 27 , 1951 ni Emily ti je alabaasise to see gbara le ati alabaakegbe to n fun mi ni isiri .
Ọgbọ́n ìkẹ́kọ̀ọ́ tí kò láfiwé , tó sì gbéṣẹ́ wo ni àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ìbẹ̀rẹ̀ lò ?
Ogbon ikekoo ti ko lafiwe , to si gbese wo ni awon Akekoo Bibeli ni ibere lo ?
“Ẹ jẹ́ alágbára, àti kí ẹ sì ní ìgboyà. Ẹ má ṣe bẹ̀rù tàbí ní ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn nítorí tí ọba Asiria àti ọ̀pọ̀ ọmọ-ogun pẹ̀lú rẹ̀, nítorí tí agbára ńlá wà pẹ̀lú wa ju òun lọ.
“E je alagbara, ati ki e si ni igboya. E ma se beru tabi ni irewesi okan nitori ti oba Asiria ati opo omo-ogun pelu re, nitori ti agbara nla wa pelu wa ju oun lo.
Báyìí, a sọ fún ilé Dafidi pé, “Aramu mà ti lẹ̀dí àpò pọ̀ mọ́ Efraimu”; fún ìdí èyí, ọkàn Ahasi àti àwọn ènìyàn rẹ̀ wárìrì gẹ́gẹ́ bí igi oko ṣe ń wárìrì níwájú afẹ́fẹ́.
Bayii, a so fun ile Dafidi pe, “Aramu ma ti ledi apo po mo Efraimu”; fun idi eyi, okan Ahasi ati awon eniyan re wariri gege bi igi oko se n wariri niwaju afefe.
Omi bo gbogbo àwọn erékùṣù, a kò sì rí ẹyọ òkè kan mọ́.
Omi bo gbogbo awon erekusu, a ko si ri eyo oke kan mo.
Gómìnà Akinwunmi Àmbọ̀dé ni lati wá àtúnṣe si iyà ti ojú ará ilú nri nípa gbi gbé ọkàn lé ọkọ̀ ilẹ́ fún ohun irinna nikan, nípa pi pari iṣẹ́ ọkọ̀ ojú irin àti ibùdókọ̀ ojú omi ti Ijọba Gómìnà Babátúndé Raji Fáṣọlá bẹ̀rẹ̀, ki wọn si ṣe kun nípa ipèsè ibùdókọ òfúrufú àti ohun amáyédẹrùn yoku
Gomina Akinwunmi Ambode ni lati wa atunse si iya ti oju ara ilu nri nipa gbi gbe okan le oko ile fun ohun irinna nikan, nipa pi pari ise oko oju irin ati ibudoko oju omi ti Ijoba Gomina Babatunde Raji Fasola bere, ki won si se kun nipa ipese ibudoko ofurufu ati ohun amayederun yoku
Boasi gbé Rutu ní ìyàwó.
Boasi gbe Rutu ni iyawo.
Kí ni ipa tí Ìwé Mímọ́ ń ní lórí àwọn Kristẹni tòótọ́ ?
Ki ni ipa ti Iwe Mimo n ni lori awon Kristeni tooto ?
▪ Ìgbà wo ni èmi àti ọkọ tàbí aya mi gbàdúrà pa pọ̀ kẹ́yìn ?
# Igba wo ni emi ati oko tabi aya mi gbadura pa po keyin ?
Ni ọjọ Kejidinlọ́gbọ̀n, oṣù Keje, ọdún Ẹgbãlemẹ͂dógún, iroyin jade ninú àwọn iwé-iroyin àti ori ayélujára pé Ọba Okunade Sijuwade, Olúbùṣe Keji, pa ipò da ni Ilú Ọba.
Ni ojo Kejidinlogbon, osu Keje, odun Egbalemedogun, iroyin jade ninu awon iwe-iroyin ati ori ayelujara pe Oba Okunade Sijuwade, Olubuse Keji, pa ipo da ni Ilu Oba.
Àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́ta wo la lè ronú lé táá jẹ́ ká lè ṣèpinnu tó tọ́ nígbà tá a bá gba ìsọfúnni èyíkéyìí ?
Awon ilana Bibeli meta wo la le ronu le taa je ka le sepinnu to to nigba ta a ba gba isofunni eyikeyii ?
Ohun tó ń da ọ̀pọ̀ wọn láàmú ni pé ojú ẹ̀dá èèyàn ni wọ́n fi ń wo ọ̀ràn náà , wọ́n ń tẹnu mọ́ àwọn nǹkan tara tí Jèhófà pèsè nínú aginjù nígbà ayé Mósè .
Ohun to n da opo won laamu ni pe oju eda eeyan ni won fi n wo oran naa , won n tenu mo awon nnkan tara ti Jehofa pese ninu aginju nigba aye Mose .
․ ․ ․ ․ ․
. . . . .
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
OJU IWOYE BIBELI
Àmọ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ ilé - dé - ilé tá a ń ṣe yìí bá Ìwé Mímọ́ mu , ìfẹ́ tá a ní fún Ọlọ́run àti fún àwọn aládùúgbò wa ló sì ń sún wa láti jẹ́rìí lọ́nà yìí .
Amo ise ojise ile - de - ile ta a n se yii ba Iwe Mimo mu , ife ta a ni fun Olorun ati fun awon aladuugbo wa lo si n sun wa lati jerii lona yii .
Àwọn òbí lè múra ọmọ wọn sílẹ̀ fún ìgbéyàwó nípa ríràn wọ́n lọ́wọ́ láti lóye ìjẹ́pàtàkì títẹ̀lé ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run .
Awon obi le mura omo won sile fun igbeyawo nipa riran won lowo lati loye ijepataki titele itosona Olorun .
Tọ́kọ rẹ̀ bá wá pa dà mọ̀ nípa rẹ̀ , kí ló máa ṣẹlẹ̀ ?
Toko re ba wa pa da mo nipa re , ki lo maa sele ?
[ Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 9 ]
[ Aworan Credit Line to wa ni oju iwe 9 ]
• Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà gbà ń fi ìdájọ́ òdodo rẹ̀ hàn ?
* Awon ona wo ni Jehofa gba n fi idajo ododo re han ?
Àbí èyí tí kò dájú pé àwọn olùṣèwádìí máa rí mú jáde níbi tí wọ́n ti ń wá àwọn àfọ́kù pákó tọ́jọ́ ẹ̀ ti pẹ́ lórí òkè tó ti di yìnyín gbagidi ?
Abi eyi ti ko daju pe awon olusewadii maa ri mu jade nibi ti won ti n wa awon afoku pako tojo e ti pe lori oke to ti di yinyin gbagidi ?
Ámúnónì sì wí fún un pé, Dìde, kí o sì máa lọ! Òun sì wí fún un pé, Kó ha ní ìdí bí! Lílé tí ìwọ ń lé mi yìí burú ju èyí tí ìwọ ti ṣe sí mi lọ
Amunoni si wi fun un pe, Dide, ki o si maa lo! Oun si wi fun un pe, Ko ha ni idi bi! Lile ti iwo n le mi yii buru ju eyi ti iwo ti se si mi lo
báyìí ó yára wọ inú ihò rệ lọ ó gbé ibọn mi jáde, wéré ó fì ibọn mi bọ ẹnu ó ni ki ng máa fì ọwộ ra á ni idi. Ẹyẹ fệệ fò wộn sọ òkò si i ni ộran náà bộ si, mo gbé ibọn mi lộwộ mo sá a, ó dun, ọkùnrin yìí si subú lulệ, ó kú.
bayii o yara wo inu iho re lo o gbe ibon mi jade, were o fi ibon mi bo enu o ni ki ng maa fi owo ra a ni idi. Eye fee fo won so oko si i ni oran naa bo si, mo gbe ibon mi lowo mo sa a, o dun, okunrin yii si subu lule, o ku.
Ó sì mú owó dínárì méjì jáde ní ọjọ́ kejì , ó fi fún olùtọ́jú ilé èrò náà , ó sì wí pé , ‘ Tọ́jú rẹ̀ , ohun yòówù tí ìwọ bá sì ná ní àfikún sí èyí , èmi yóò san án padà fún ọ nígbà tí mo bá padà wá síhìn - ín . ’
O si mu owo dinari meji jade ni ojo keji , o fi fun olutoju ile ero naa , o si wi pe , ‘ Toju re , ohun yoowu ti iwo ba si na ni afikun si eyi , emi yoo san an pada fun o nigba ti mo ba pada wa sihin - in . ’
[ Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ]
[ Alaye isale iwe ]
Bí àpẹẹrẹ , wo bí Jèhófà ṣe bójú tó Jeremáyà nígbà hílàhílo tó yọrí sí ìparun Jerúsálẹ́mù lọ́dún 607 ṣáájú Sànmánì Kristẹni .
Bi apeere , wo bi Jehofa se boju to Jeremaya nigba hilahilo to yori si iparun Jerusalemu lodun 607 saaju Sanmani Kristeni .
[ Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ]
[ Alaye isale iwe ]
Alábòójútó àyíká kan àti ìyàwó rẹ̀ fẹ́ rìnrìn - àjò lọ sí ìjọ míì tí wọ́n fẹ́ bẹ̀ wò .
Alaboojuto ayika kan ati iyawo re fe rinrin - ajo lo si ijo mii ti won fe be wo .
Igi kì í dá lóko kó pa ará ilé.
Igi ki i da loko ko pa ara ile.
Wọ́n dìtẹ̀ sí i ní Jerusalẹmu, ó sì sálọ sí Lakiṣi, ṣùgbọ́n wọ́n rán àwọn ọkùnrin tẹ̀lé e sí Lakiṣi, wọ́n sì pa á síbẹ̀.
Won dite si i ni Jerusalemu, o si salo si Lakisi, sugbon won ran awon okunrin tele e si Lakisi, won si pa a sibe.
A gbà , èyí sí já sí ìbùkún ńláǹlà fún wa .
A gba , eyi si ja si ibukun nlanla fun wa .
Kò sí ẹni tó máa ń fẹ́ kí àwọn èèyàn pa òun tì , yálà ó jẹ́ ọ̀dọ́ tàbí àgbàlagbà .
Ko si eni to maa n fe ki awon eeyan pa oun ti , yala o je odo tabi agbalagba .
Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù fi sọ ojú abẹ níkòó nínú lẹ́tà tó kọ sí àwọn Hébérù tó jẹ́ Kristẹni ?
Ki nidi ti Poolu fi so oju abe nikoo ninu leta to ko si awon Heberu to je Kristeni ?
Àwọn itọkasi
Awon itokasi
Síbẹ̀ , kò sí bí wọn ò ṣe ní gbọ́rọ̀ wa torí pé ketekete ni wọ́n ń gbọ́ ohùn ìwàásù tó ń bú jáde látinú àwọn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ náà nínú ilé wọn .
Sibe , ko si bi won o se ni gboro wa tori pe ketekete ni won n gbo ohun iwaasu to n bu jade latinu awon oko ayokele naa ninu ile won .
21. Lẹ̀hìn náà, Ô ṣe ẹ̀nà náà ni
21. Lehin naa, O se ena naa ni
Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sọ fún un pé, “Ǹjẹ́ o mọ̀ pé nígbà tí àwọn Farisi gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, ó bí wọn ninu?”
Nigba naa ni awon omo-eyin re wa sodo re, won so fun un pe, "Nje o mo pe nigba ti awon Farisi gbo oro re, o bi won ninu?"
Èkíní , wọ́n rántí àṣẹ tí Jésù pa fún àpọ́sítélì Pétérù nígbà tó fi idà gbèjà Jésù , pé : “ Dá idà rẹ padà sí àyè rẹ̀ , nítorí gbogbo àwọn tí wọ́n bá ń mú idà yóò ṣègbé nípasẹ̀ idà . ”
Ekini , won ranti ase ti Jesu pa fun apositeli Peteru nigba to fi ida gbeja Jesu , pe : “ Da ida re pada si aye re , nitori gbogbo awon ti won ba n mu ida yoo segbe nipase ida . ”
Ó ti wá ṣe kedere pé ìṣàkóso Mèsáyà kò ní di ìdàkudà láé , a ó sì máa jàǹfààní Ìjọba yìí títí láé !
O ti wa se kedere pe isakoso Mesaya ko ni di idakuda lae , a o si maa janfaani Ijoba yii titi lae !
Ó sì búra fún un wí pé, “Ohunkóhun tí ìwọ bá fẹ́, ìbá à ṣe ìdajì ìjọba mi ni, èmi yóò fi fún ọ.”
O si bura fun un wi pe, "Ohunkohun ti iwo ba fe, iba a se idaji ijoba mi ni, emi yoo fi fun o."
Wọ́n tún ń darí nǹkan bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé lọ́fẹ̀ẹ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ .
Won tun n dari nnkan bi egberun lona aadota ikekoo Bibeli inu ile lofee losoose .
Ọ̀pọ̀ nǹkan táa fi wúrà ṣe , táa ṣàwárí nínú àwọn ọkọ̀ òkun tó rì àti nínú àwọn nǹkan mìíràn ṣì ń dán gbinrin lẹ́yìn ọgọ́rọ̀ọ̀rún ọdún .
Opo nnkan taa fi wura se , taa sawari ninu awon oko okun to ri ati ninu awon nnkan miiran si n dan gbinrin leyin ogoroorun odun .
Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Wà Níbi Gbogbo Nígbà Gbogbo ?
Se Olorun Maa N Wa Nibi Gbogbo Nigba Gbogbo ?
( b ) Ìkìlọ̀ wo ni Pọ́ọ̀lù fúnni ?
( b ) Ikilo wo ni Poolu funni ?
Àmọ́ ẹni tó fàbùkù kàn lọ́tẹ̀ yìí máa bu ú lọ́wọ́ , ó ti fàbùkù kan olórí àwọn ọmọ ogun kan , ẹni tó láwọn ọmọ ogun tó kọ́ṣẹ́ mọṣẹ́ tí wọ́n sì nífẹ̀ẹ́ ọ̀gá wọn .
Amo eni to fabuku kan lote yii maa bu u lowo , o ti fabuku kan olori awon omo ogun kan , eni to lawon omo ogun to kose mose ti won si nifee oga won .
Àwa Kristẹni òde òní lè rí ẹ̀kọ́ kọ́ lára Pọ́ọ̀lù . Ó fìtara ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ , ó sì jẹ́ kó ṣe kedere pé inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí Ọlọ́run fi hàn sóun kò “ já sí asán . ”
Awa Kristeni ode oni le ri eko ko lara Poolu . O fitara se ise ojise re , o si je ko se kedere pe inu rere ailetoosi ti Olorun fi han soun ko “ ja si asan . ”
Bí o bá ń ṣe àwíjàre rẹ níwájú aládùúgbò rẹ,má ṣe tú àṣírí tí ẹlòmíràn ní lọ́dọ̀ rẹ,
Bi o ba n se awijare re niwaju aladuugbo re,ma se tu asiri ti elomiran ni lodo re,
Kódà níbi tọ́rọ̀ dé dúró yìí , ṣe ni ìgbésí ayé wa rí bí Jóòbù , ẹni àtijọ́ náà , ṣe ṣàlàyé rẹ̀ nígbà tó sọ nípa èèyàn pé : “ Ọlọ́jọ́ kúkúrú ni , ó sì kún fún ṣìbáṣìbo . ” — Jóòbù 14 : 1 .
Koda nibi toro de duro yii , se ni igbesi aye wa ri bi Joobu , eni atijo naa , se salaye re nigba to so nipa eeyan pe : “ Olojo kukuru ni , o si kun fun sibasibo . ” — Joobu 14 : 1 .
nítorí ìbínú ní ímú ìjìyà wá nípa ìdà Kí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ pé ìdájọ́ kan ń bẹ
nitori ibinu ni imu ijiya wa nipa ida Ki eyin ki o le mo pe idajo kan n be
Ẹni tó bá gba òfin yìí gbọ́ sábà máa ń gba kámú pé ìyà tó tọ́ sí òun àti àwọn ẹlòmíràn làwọn ń jẹ .
Eni to ba gba ofin yii gbo saba maa n gba kamu pe iya to to si oun ati awon elomiran lawon n je .
Báwo làwọn Kristẹni tòótọ́ ṣe ń lo àwọn ohun àmúṣọrọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn orílẹ̀ - èdè ?
Bawo lawon Kristeni tooto se n lo awon ohun amusoro lati odo awon orile - ede ?
Ó wá ṣe kedere pé Jairo ti ya ara rẹ̀ sí mímọ́ fún Jèhófà .
O wa se kedere pe Jairo ti ya ara re si mimo fun Jehofa .
Pẹ̀lú bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ sí nínú ayé , kò sídìí kankan fún àwọn Kristẹni láti páyà tàbí láti bẹ̀rù .
Pelu bi gbogbo nnkan se n lo si ninu aye , ko sidii kankan fun awon Kristeni lati paya tabi lati beru .
Àwọn àlàyé tí Fílípì ṣe wọ ìjòyè yẹn lọ́kàn gan - an , inú ẹ̀ sì dùn débi pé ó pinnu láti di Kristẹni . — Ìṣe 8 : 35 - 39 .
Awon alaye ti Filipi se wo ijoye yen lokan gan - an , inu e si dun debi pe o pinnu lati di Kristeni . — Ise 8 : 35 - 39 .
Jèhófà yára wá nǹkan ṣe sí ọ̀ràn náà nípa gbígbé nǹkan gba ọ̀nà míì kí ète rẹ̀ bàa lè ní ìmúṣẹ .
Jehofa yara wa nnkan se si oran naa nipa gbigbe nnkan gba ona mii ki ete re baa le ni imuse .
Mátíù tẹnu mọ́ ọ̀rọ̀ nípa Ìjọba Ọlọ́run
Matiu tenu mo oro nipa Ijoba Olorun
Ó fi kíkorò ojú àti ìbínú ńlá gbé ilẹ̀ mì, bẹ́ẹ̀ ni òun kò sì gbàá gbọ́ pé, ìró ipè ni
O fi kikoro oju ati ibinu nla gbe ile mi, bee ni oun ko si gbaa gbo pe, iro ipe ni
Báwo lo ṣe lè ṣe é tí ojúṣe kan ò ní pa òmíràn lára tí wàá sì máa ní “ ìdùnnú Jèhófà ” ? — Neh .
Bawo lo se le se e ti ojuse kan o ni pa omiran lara ti waa si maa ni “ idunnu Jehofa ” ? — Neh .
Bíbélì sọ pé : “ Láti ara ọkùnrin kan ni [ Ọlọ́run ] ti dá gbogbo orílẹ̀ - èdè àwọn ènìyàn , láti máa gbé ní ojú gbogbo ilẹ̀ ayé pátá . ”
Bibeli so pe : “ Lati ara okunrin kan ni [ Olorun ] ti da gbogbo orile - ede awon eniyan , lati maa gbe ni oju gbogbo ile aye pata . ”
“Ẹ̀wẹ̀, wí fún ìdílé ọba Juda pé, ‘Gbọ́ ọ̀rọ̀ .
"Ewe, wi fun idile oba Juda pe, 'Gbo oro .
Nígbà tó ń gbàdúrà sí Ọlọ́run tòótọ́ , ó bẹ̀bẹ̀ pé : “ Gbọ́ ohùn mi .
Nigba to n gbadura si Olorun tooto , o bebe pe : “ Gbo ohun mi .
Àwọn Ọmọ Àfànítẹ̀ẹ̀tẹ́ àti Tẹlifíṣọ̀n
Awon Omo Afaniteete ati Telifison
Dída ìsìn pọ̀ mọ́ ìṣèlú lọ́nà àìmọ́ yìí ti gbé ìsìn mímọ́ gaara tí Jésù fi kọ́ni gbòdì pátápátá .
Dida isin po mo iselu lona aimo yii ti gbe isin mimo gaara ti Jesu fi koni gbodi patapata .
Tí kì í bá ṣe ti irúgbìn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tó ṣì ń bu ẹwà kún àwọn òkè ayọnáyèéfín tó wà nínú ọgbà yìí , ibẹ̀ ì bá ti dahoro .
Ti ki i ba se ti irugbin to sara oto to si n bu ewa kun awon oke ayonayeefin to wa ninu ogba yii , ibe i ba ti dahoro .
Ṣe àwọn ìpinnu tó máa mú kó o gbádùn bó o ṣe ń sin Jèhófà láwọn àkókò amóríyá yìí . — Sm .
Se awon ipinnu to maa mu ko o gbadun bo o se n sin Jehofa lawon akoko amoriya yii . — Sm .
Nígbà tó fún Tiffany láyè láti ṣàlàyé àsọtẹ́lẹ̀ náà , ó dìde , ó sì sọ̀rọ̀ geere láìjẹ́ pé ó ti múra sílẹ̀ tẹ́lẹ̀ .
Nigba to fun Tiffany laye lati salaye asotele naa , o dide , o si soro geere laije pe o ti mura sile tele .
Ó dára láti mú ọ̀kankí o má sì ṣe fi èkejì sílẹ̀Ọkùnrin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run yóò bọ́ lọ́wọ́ gbogbo àrékérekè.
O dara lati mu okanki o ma si se fi ekeji sileOkunrin ti o beru Olorun yoo bo lowo gbogbo arekereke.