diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
kú má jẹ k arùn
ku ma je k arun
Ẹ Má Ṣe Wo “ Àwọn Ohun Tí Ń Bẹ Lẹ́yìn ”
E Ma Se Wo “ Awon Ohun Ti N Be Leyin ”
Àwọn eniyan ń kígbe lé wọn lórí pé;“Ẹ máa lọ! Ẹ̀yin aláìmọ́!Ẹ máa kóra yín lọ! Ẹ má fi ọwọ́ kan nǹkankan!”Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe di ìsáǹsá ati alárìnkiri,nítorí àwọn eniyan ń wí láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè pé,“Àwọn wọnyi kò gbọdọ̀ bá wa gbé pọ̀ mọ́.”
Awon eniyan n kigbe le won lori pe;“E maa lo! Eyin alaimo!E maa kora yin lo! E ma fi owo kan nnkankan!”Bee ni won se di isansa ati alarinkiri,nitori awon eniyan n wi laarin gbogbo orile-ede pe,“Awon wonyi ko gbodo ba wa gbe po mo.”
Kí ni mo lè ṣe tí èmi àti ọmọ mi á fi lè máa bá ara wa sọ̀rọ̀ láìsí àríyànjiyàn ?
Ki ni mo le se ti emi ati omo mi a fi le maa ba ara wa soro laisi ariyanjiyan ?
Nípa èyí, wọ́n yóò lè máa kọ́ àwọn òdóbìnrin láti nífẹ̀ẹ́ àwọn ọkọ wọn àti àwọn ọmọ wọn, láti jẹ́ ẹni ìwọ̀ntúnwọ̀nsì àti ọlọ́kàn mímọ́, kí wọ́n máa ṣe ojúse wọn nínú ilé, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ onínú rere, kí wón sì máa tẹríba fún àwọn ọkọ wọ́n, kí ẹnikẹ́ni máa baà sọ̀rọ̀ òdì sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
Nipa eyi, won yoo le maa ko awon odobinrin lati nifee awon oko won ati awon omo won, lati je eni iwontunwonsi ati olokan mimo, ki won maa se ojuse won ninu ile, won gbodo je oninu rere, ki won si maa teriba fun awon oko won, ki enikeni maa baa soro odi si oro Olorun
129. Ní ọjọ tí Òun yòò kò gbogbo
129. Ni ojo ti Oun yoo ko gbogbo
Ó sọ fún Tímótì , Kristẹni ọ̀dọ́ tó jẹ́ alábòójútó pé : “ Má ṣe fi àṣìṣe àgbà ọkùnrin hàn lọ́nà mímúná janjan .
O so fun Timoti , Kristeni odo to je alaboojuto pe : " Ma se fi asise agba okunrin han lona mimuna janjan .
Ó dájú pé ṣe ni ọ̀pọ̀ nínú wọn á máa fi Nóà àti ìdílé rẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́ , àwọn míì tiẹ̀ lè lérí léka sí i , kí wọ́n sì fìbínú ta kò ó .
O daju pe se ni opo ninu won a maa fi Noa ati idile re se yeye , awon mii tie le leri leka si i , ki won si fibinu ta ko o .
Ni àwọn tí wọ́n jọ mọra ní ṣọ́ọ̀ṣì bá bẹ̀rẹ̀ sí fi wọ́n ṣe yẹ̀yẹ́ .
Ni awon ti won jo mora ni soosi ba bere si fi won se yeye .
Báwo ni ẹ̀yin ọ̀dọ́ ṣe lè máa fọwọ́ sowọ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn òbí yín kí ìdílé yín lè máa “ wà lójúfò ” nípa tẹ̀mí ?
Bawo ni eyin odo se le maa fowo sowo po pelu awon obi yin ki idile yin le maa “ wa lojufo ” nipa temi ?
“ Ìhìn rere ìjọba Ọlọ́run ” ni Jésù wàásù rẹ̀ , ohun tó sì retí pé káwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ náà máa ṣe nìyẹn .
“ Ihin rere ijoba Olorun ” ni Jesu waasu re , ohun to si reti pe kawon omo eyin re naa maa se niyen .
láàrin ara yin, kì yoò sí ẹ̀ṣẹ̀ fún
laarin ara yin, ki yoo si ese fun
Bíbélì kíkà tá a dábàá fún January
Bibeli kika ta a dabaa fun January
Nígbà tó sì jẹ́ pé àárín ayé Sátánì là ń gbé , a gbọ́dọ̀ ṣọ́ra kí ẹ̀mí ayé yẹn má bàa ràn wá .
Nigba to si je pe aarin aye Satani la n gbe , a gbodo sora ki emi aye yen ma baa ran wa .
Nítorí pé Júdà àti Ísírẹ́lì ni Ọlọ́run wọn tí í se Olúwa alágbára kò gbàgbọ́ bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ilé wọn kún fún kìki ẹ̀bi níwájú ẹni mímọ́ Ísírẹ́lì
Nitori pe Juda ati Isireli ni Olorun won ti i se Oluwa alagbara ko gbagbo bi o tile je pe ile won kun fun kiki ebi niwaju eni mimo Isireli
Torí náà ó sọ pé : “ Ńṣe ni ẹsẹ̀ mi àti ọwọ́ mi ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ , eyín mi sì ń lù mọ́ra wọn keke .
Tori naa o so pe : “ Nse ni ese mi ati owo mi n gbon pepe , eyin mi si n lu mora won keke .
Wọ́n ó sì sọ fún àwọn olùgbé ilẹ̀ yìí
Won o si so fun awon olugbe ile yii
gbigbé
gbigbe
Àmọ́ , kí ló mú káwọn èèyàn mọ̀ ọ́n nílé lóko ?
Amo , ki lo mu kawon eeyan mo on nile loko ?
Lawrence Cunningham , tó jẹ́ ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ní Yunifásítì Notre Dame , sọ pé : “ Àwọn èèyàn máa ń nífẹ̀ẹ́ sí ohun tó bá ti jẹ mọ́ ìjẹ́mímọ́ láyé yìí .
Lawrence Cunningham , to je elekoo isin ni Yunifasiti Notre Dame , so pe : " Awon eeyan maa n nifee si ohun to ba ti je mo ijemimo laye yii .
Bí àpẹẹrẹ , ǹjẹ́ a lè máa retí ìbùkún Jèhófà lórí ọ̀nà ìgbésí ayé kan tó fi ohun tẹ̀mí sí ipò kejì ?
Bi apeere , nje a le maa reti ibukun Jehofa lori ona igbesi aye kan to fi ohun temi si ipo keji ?
Pelatiah, Hanani, Anaiah,
Pelatiah, Hanani, Anaiah,
mísaẹ́lì
misaeli
Ohun kan ṣoṣo tó lè mú ká jogún ìyè àìnípẹ̀kun ni pé ká ‘ gba ìmọ̀ ’ Jèhófà ká sì máa “ lo ìgbàgbọ́ ” nínú Jésù , Ọmọ bíbí rẹ̀ kan ṣoṣo .
Ohun kan soso to le mu ka jogun iye ainipekun ni pe ka ‘ gba imo ’ Jehofa ka si maa “ lo igbagbo ” ninu Jesu , Omo bibi re kan soso .
Ahiamu, ọmọ Sakari, ará Harari, ati Elifali, ọmọ Uri;
Ahiamu, omo Sakari, ara Harari, ati Elifali, omo Uri;
43.. Àwọn wọnyí ni wWỌn. Jẹ
43.. Awon wonyi ni wWOn. Je
ÈÉRÚN KÈRÉKÈRÉ TÓ TI BÀ JẸ́
EERUN KEREKERE TO TI BA JE
▪ Àwọn adájọ́ ní láti ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe láti gba ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn kàn náà sílẹ̀
▪ Awon adajo ni lati se gbogbo ohun ti won le se lati gba eni ti won fesun kan naa sile
Ẹ̀kọ́ Bíbélì tí mo ti kọ́ ń jó nínú mi bí iná .
Eko Bibeli ti mo ti ko n jo ninu mi bi ina .
Kí ni àpèjúwe yìí fi hàn nípa ìdí tó fi yẹ ká tẹpẹlẹ mọ́ àdúrà gbígbà ?
Ki ni apejuwe yii fi han nipa idi to fi ye ka tepele mo adura gbigba ?
Ǹjẹ́ ìyẹn ì bá mú ìyìn bá Ọlọ́run ?
Nje iyen i ba mu iyin ba Olorun ?
kíryat-árbà
kiryat-arba
Àwọn Ọmọ Rẹ Ń Wò Ẹ́ O !
Awon Omo Re N Wo E O !
Nígbà tí Jèhófà ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn kan tó pa Òfin rẹ̀ mọ́ , ó tipasẹ̀ Aísáyà wòlíì rẹ̀ sọ pé : “ Àní èmi yóò fún wọn ní ohun ìránnilétí àti orúkọ ní ilé mi àti nínú àwọn ògiri mi . . .
Nigba ti Jehofa n soro nipa awon kan to pa Ofin re mo , o tipase Aisaya wolii re so pe : “ Ani emi yoo fun won ni ohun irannileti ati oruko ni ile mi ati ninu awon ogiri mi . . .
Yàtọ̀ síyẹn , àwọn orí tó ṣáájú nínú ìwé Jẹ́nẹ́sísì lo oòrùn àti òṣùpá láti fi ìyàtọ̀ kedere hàn láàárín bí ọdún ṣe máa ń yí po àti bí oṣù ṣe máa ń yí po . — Jẹ́nẹ́sísì 1 : 14 - 16 ; 7 : 11 .
Yato siyen , awon ori to saaju ninu iwe Jenesisi lo oorun ati osupa lati fi iyato kedere han laaarin bi odun se maa n yi po ati bi osu se maa n yi po . -- Jenesisi 1 : 14 - 16 ; 7 : 11 .
Hamu tí í ṣe baba Kenaani sì rí baba rẹ̀ ní ìhòhò bẹ́ẹ̀ ni ó sì lọ sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ méjèèjì ní ìta.
Hamu ti i se baba Kenaani si ri baba re ni ihoho bee ni o si lo so fun awon arakunrin re mejeeji ni ita.
tí yìnyín bo odò náà tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi ṣókùnkùn,tí yìnyín ńláńlá sì farapamọ́ sibẹ,
ti yinyin bo odo naa tobee ti o fi sokunkun,ti yinyin nlanla si farapamo sibe,
Ó fi wá lọ́kàn balẹ̀ , ó ní : “ Ẹ lè wà nílé àwọn míṣọ́nnárì títí dìgbà tí Bill yóò fi ríṣẹ́ . ”
O fi wa lokan bale , o ni : “ E le wa nile awon misonnari titi digba ti Bill yoo fi rise . ”
Ǹjẹ́ a lè gba ìkógun lọ́wọ́ alágbára,tabi kí á gba òǹdè lọ́wọ́ òkúrorò eniyan?
Nje a le gba ikogun lowo alagbara,tabi ki a gba onde lowo okuroro eniyan?
Wọ́n ń dúró de ọkọ mi àti Pál Nagypál tí wọ́n dé kẹ́yìn .
Won n duro de oko mi ati Pal Nagypal ti won de keyin .
Ìran rẹ̀ ni ìran keje látọ̀dọ̀ Ádámù .
Iran re ni iran keje latodo Adamu .
Bíbélì ṣàlàyé pé ìfẹ́ ló mú kí Jèhófà dá tọkọtaya àkọ́kọ́ láìsí pé wọ́n ń ṣàìsàn tàbí pé wọ́n ń kú .
Bibeli salaye pe ife lo mu ki Jehofa da tokotaya akoko laisi pe won n saisan tabi pe won n ku .
Bí àpẹẹrẹ , obìnrin kan tó jẹ́ Kristẹni kédàárò pé ó máa ń dun òun gan - an pé lẹ́yìn lílọ sí ìpàdé tí ń gbéni ró , òun kò lè délé kóun sì bá ọkọ òun aláìgbàgbọ́ jíròrò àwọn nǹkan tẹ̀mí .
Bi apeere , obinrin kan to je Kristeni kedaaro pe o maa n dun oun gan - an pe leyin lilo si ipade ti n gbeni ro , oun ko le dele koun si ba oko oun alaigbagbo jiroro awon nnkan temi .
GẸ́GẸ́ bí dókítà oníṣẹ́ abẹ kan ṣe máa ń dáàbò bo àwọn aláìsàn tó ń tọ́jú nípa fífọ ọwọ́ rẹ̀ , nípa fífi omi gbígbóná pa àwọn kòkòrò tó lè wà lára àwọn irinṣẹ́ rẹ̀ , nípa mímú kí yàrá tó ti ń ṣiṣẹ́ abẹ náà wà ní mímọ́ tónítóní , ìwọ náà lè dáàbò bo ìdílé rẹ nípa ṣíṣe ìmọ́tótó ara rẹ , ilé ìdáná rẹ àti oúnjẹ rẹ .
GEGE bi dokita onise abe kan se maa n daabo bo awon alaisan to n toju nipa fifo owo re , nipa fifi omi gbigbona pa awon kokoro to le wa lara awon irinse re , nipa mimu ki yara to ti n sise abe naa wa ni mimo tonitoni , iwo naa le daabo bo idile re nipa sise imototo ara re , ile idana re ati ounje re .
Ẹ̀kọ́ wo ni pípèsè tí Jèhófà pèsè mánà kọ́ wa ?
Eko wo ni pipese ti Jehofa pese mana ko wa ?
Ó dájú pé Ọlọ́run ò ní pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n ré òfin òun kọjá tán , kó tún wá sọ pé ikú ló tọ́ sí wọn nítorí pé wọ́n pa àṣẹ òun mọ́ !
O daju pe Olorun o ni pase fun won pe ki won re ofin oun koja tan , ko tun wa so pe iku lo to si won nitori pe won pa ase oun mo !
Arábìnrin kan tó ti ń sìn ní Bẹ́tẹ́lì fún ọdún bíi mélòó kan sọ pé : “ Ìgbésí ayé àwọn òbí mi nínú iṣẹ́ ìsìn Jèhófà ni ohun tó fún mi lágbára gan - an láti wọnú iṣẹ́ ìsìn Bẹ́tẹ́lì .
Arabinrin kan to ti n sin ni Beteli fun odun bii meloo kan so pe : “ Igbesi aye awon obi mi ninu ise isin Jehofa ni ohun to fun mi lagbara gan - an lati wonu ise isin Beteli .
Nígbà tí ó rẹ ọkàn mi nínú mi, èmi rántí rẹ, Olúwa , àdúrà mi sì wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, nínú tẹ́ḿpìlì mímọ́ rẹ
Nigba ti o re okan mi ninu mi, emi ranti re, Oluwa , adura mi si wa si odo re, ninu tempili mimo re
Báwo ni ìhìn tó tinú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wá ṣe lágbára tó ?
Bawo ni ihin to tinu Oro Olorun wa se lagbara to ?
Nítorí pé Ọlọ́run ti fún Jésù ní agbára àti àṣẹ láti fún àwọn tó bá ṣègbọràn ní ìyè ayérayé lórí ilẹ̀ ayé , ó wá tipa bẹ́ẹ̀ di “ Baba Ayérayé ” fún wọn .
Nitori pe Olorun ti fun Jesu ni agbara ati ase lati fun awon to ba segboran ni iye ayeraye lori ile aye , o wa tipa bee di " Baba Ayeraye " fun won .
Àmọ́ ṣá o , wá àkókò tí ìwọ àti ìdílé rẹ á fi máa rántí “ gbogbo ẹgbẹ́ àwọn ará [ wa ] nínú ayé . ”
Amo sa o , wa akoko ti iwo ati idile re a fi maa ranti “ gbogbo egbe awon ara [ wa ] ninu aye . ”
Nígbà tí màá fi sún mọ́ ọmọ ogún ọdún , mo ti ń wá ẹni tí màá máa bá ní ìbálópọ̀ ( ì báà jẹ́ ọkùnrin tàbí obìnrin ) níbikíbi tí mo bá ti lè rí wọn , ì báà jẹ́ nílé ọtí , láwọn ilé fàájì alaalẹ́ , kódà ní ṣọ́ọ̀ṣì pàápàá .
Nigba ti maa fi sun mo omo ogun odun , mo ti n wa eni ti maa maa ba ni ibalopo ( i baa je okunrin tabi obinrin ) nibikibi ti mo ba ti le ri won , i baa je nile oti , lawon ile faaji alaale , koda ni soosi paapaa .
INÚ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń dùn láti jíròrò Bíbélì pẹ̀lú àwọn èèyàn .
INU awon Elerii Jehofa maa n dun lati jiroro Bibeli pelu awon eeyan .
Wọ́n tún máa ń bójú tó àwọn iṣẹ́ mìíràn tó máa ń gba àkókò àmọ́ tí wọ́n jẹ́ iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì .
Won tun maa n boju to awon ise miiran to maa n gba akoko amo ti won je ise to se pataki .
olódodo jù nyín lọ, nítorítí nwọ́n kò ṣẹ̀ sí ìmọ̀ nlá nì èyítí ẹ̀yin ti rí gbà; nítorínã ni Ọlọ́run yíò fi ṣãnú fún nwọn; bẹ̃ni, yíò mú kí ọjọ́ nwọn gùn yíò sì mú kí iní-ọmọ nwọn ó pọ̀ síi, àní nígbàtí a ó pa nyín run pátápátá àfi bí ẹ̀yin bá ronúpìwàdà.
olododo ju nyin lo, nitoriti nwon ko se si imo nla ni eyiti eyin ti ri gba; nitorina ni Olorun yio fi sanu fun nwon; beni, yio mu ki ojo nwon gun yio si mu ki ini-omo nwon o po sii, ani nigbati a o pa nyin run patapata afi bi eyin ba ronupiwada.
Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe lè yí ẹnì kan padà tó ?
Bawo ni Oro Olorun se le yi eni kan pada to ?
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 25 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 25 ]
Arákùnrin Vaca ń fi ìṣòtítọ́ sìn nìṣó gẹ́gẹ́ bí alàgbà àti aṣáájú - ọ̀nà àkànṣe .
Arakunrin Vaca n fi isotito sin niso gege bi alagba ati asaaju - ona akanse .
Àwọn ẹranko tí pátakò wọn kò là tan tàbí tí wọn kò jẹ àpọ̀jẹ jẹ́ àìmọ́ fún yín
Awon eranko ti patako won ko la tan tabi ti won ko je apoje je aimo fun yin
BÓ O bá fi àmì ✔ sẹ́gbẹ̀ẹ́ “ Kò ṣẹlẹ̀ rí , ” “ Kò sí , ” tí o kò sì kọ ohunkóhun sínú àlàfo tó kẹ́yìn , a bá ẹ yọ̀ , a jẹ́ pé o kì í bínú sódì nìyẹn !
BO O ba fi ami segbee " Ko sele ri , " " Ko si , " ti o ko si ko ohunkohun sinu alafo to keyin , a ba e yo , a je pe o ki i binu sodi niyen !
Àmọ́ kì í ṣe owó tàbí fàájì ló yẹ ká kà sí pàtàkì jù nínú ìgbésí ayé wa .
Amo ki i se owo tabi faaji lo ye ka ka si pataki ju ninu igbesi aye wa .
Ohun míì tún ni àwọn ìtẹ̀jáde tó ń ṣàlàyé Bíbélì tá à ń rí gbà lóṣooṣù .
Ohun mii tun ni awon itejade to n salaye Bibeli ta a n ri gba losoosu .
Àṣẹ pàtàkì tó fìfẹ́ hàn wo ni Jèhófà fún Ádámù ?
Ase pataki to fife han wo ni Jehofa fun Adamu ?
Epo ọkọ̀ kò kọ́kọ́ wọ́n nígbàtí Olóri-ogun Abacha gba Ìjọba ni ọdún méjìlélógún sẹhin
Epo oko ko koko won nigbati Olori-ogun Abacha gba Ijoba ni odun mejilelogun sehin
Ṣé Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ Ṣeé Gbára Lé ?
Se Eri Okan Re See Gbara Le ?
1 , 2 . ( a ) Èrò wo làwọn èèyàn ní nípa òmìnira ?
1 , 2 . ( a ) Ero wo lawon eeyan ni nipa ominira ?
Ní kúkúrú , Ọlọ́run dá ẹ̀mí Jeremáyà , Bárúkù , Ebedi - mélékì àtàwọn míì bẹ́ẹ̀ sí nígbà ìyàn , àrùn àti ikú yẹn . — Jer .
Ni kukuru , Olorun da emi Jeremaya , Baruku , Ebedi - meleki atawon mii bee si nigba iyan , arun ati iku yen . -- Jer .
Àwọn ìyípadà tí mo ṣe nínú ìwà mi fún àwọn òbí mi níṣìírí láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .
Awon iyipada ti mo se ninu iwa mi fun awon obi mi nisiiri lati kekoo Bibeli .
Lára àwọn àmì tí a ó fi mọ wíwàníhìn - ín rẹ̀ tá ò lè fojú rí ni ogun , àìtó oúnjẹ , ìsẹ̀lẹ̀ , àwọn èké wòlíì , ìwà àìlófin tó ń gbalẹ̀ àti àjàkálẹ̀ àrùn tó lágbára .
Lara awon ami ti a o fi mo wiwanihin - in re ta o le foju ri ni ogun , aito ounje , isele , awon eke wolii , iwa ailofin to n gbale ati ajakale arun to lagbara .
Dafidi ranti ilé, ó ní, “Kì bá ti dùn tó kí n rí ẹni fún mi ní omi mu láti inú kànga tí ó wà lẹ́nu ibodè Bẹtilẹhẹmu!”
Dafidi ranti ile, o ni, “Ki ba ti dun to ki n ri eni fun mi ni omi mu lati inu kanga ti o wa lenu ibode Betilehemu!”
Ìwé 1 Kọ́ríńtì 2 : 16 sọ pé ká ní “ èrò inú ti Kristi . ”
Iwe 1 Korinti 2 : 16 so pe ka ni “ ero inu ti Kristi . ”
Jèhófà tún tipasẹ̀ Kristi pèsè “ àwọn ẹ̀bùn [ tí ó jẹ́ ] ènìyàn . ”
Jehofa tun tipase Kristi pese " awon ebun [ ti o je ] eniyan . "
Nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bá dé , àwọn èèyàn yóò lè sọ nípa Jèhófà Ọlọ́run pé : “ Ìwọ ti yí àfiyèsí rẹ sí ilẹ̀ ayé , kí o lè fún un ní ọ̀pọ̀ yanturu . . .
Nigba ti Ijoba Olorun ba de , awon eeyan yoo le so nipa Jehofa Olorun pe : " Iwo ti yi afiyesi re si ile aye , ki o le fun un ni opo yanturu . . .
Bí ẹkún bá ń gbọ̀n ẹ́ , sun ún !
Bi ekun ba n gbon e , sun un !
Àwọn Kristẹni kan ti fìgbà kan rí jẹ́ olè , ajoògùnyó tàbí oníṣekúṣe .
Awon Kristeni kan ti figba kan ri je ole , ajoogunyo tabi onisekuse .
tàbi orúkọ fún ìmọràn
tabi oruko fun imoran
Ó dùn mi pé àwọn kan lára àwọn ẹbí mi ti kú torí pé wọn ò fi ìwà jàgídíjàgan sílẹ̀ .
O dun mi pe awon kan lara awon ebi mi ti ku tori pe won o fi iwa jagidijagan sile .
kẹtà-lélógún
keta-lelogun
“OLUWA yóo bukun ìkórè inú àká rẹ, ati gbogbo nǹkan tí o bá dáwọ́ lé. OLUWA Ọlọrun rẹ yóo bukun ọ ní ilẹ̀ tí ó fún ọ.
"OLUWA yoo bukun ikore inu aka re, ati gbogbo nnkan ti o ba dawo le. OLUWA Olorun re yoo bukun o ni ile ti o fun o.
Ohun yòówù káwọn olùkọ́ èké sọ , a kò ní tẹ̀ lé wọn !
Ohun yoowu kawon oluko eke so , a ko ni te le won !
Ẹni tí ó dàbí eniyan bá tún fi ọwọ́ kàn mí, ó sì fún mi ní okun.
Eni ti o dabi eniyan ba tun fi owo kan mi, o si fun mi ni okun.
Ó ṣòro fún ẹnì kan tó ń ka Bíbélì láti dá gbogbo àwọn tó sọ̀rọ̀ nínú Orin Sólómọ́nì mọ̀ , ṣùgbọ́n ó ṣeé ṣe láti mọ̀ wọ́n bá a bá ṣàgbéyẹ̀wò ohun tí wọ́n sọ tàbí ohun tí ẹlòmíì sọ sí wọn .
O soro fun eni kan to n ka Bibeli lati da gbogbo awon to soro ninu Orin Solomoni mo , sugbon o see se lati mo won ba a ba sagbeyewo ohun ti won so tabi ohun ti elomii so si won .
Bí àpẹẹrẹ , kí ló yẹ ká ṣe bí a bá dojú kọ ìdẹwò láti lọ́wọ́ nínú ohunkóhun tí Jèhófà sọ pé kò dára ?
Bi apeere , ki lo ye ka se bi a ba doju ko idewo lati lowo ninu ohunkohun ti Jehofa so pe ko dara ?
Yóò fi àwọn ọba wọn lé e yín lọ́wọ́, ẹ̀yin ó sì pa orúkọ wọn rẹ́ lábẹ́ ọ̀run
Yoo fi awon oba won le e yin lowo, eyin o si pa oruko won re labe orun
Ohun tó máa ń jẹ́ kí ìbànújẹ́ yìí légbá kan ni pé , kò sẹ́lòmíràn tó “ mọ ” ọmọ náà tó bí ìyá yẹn ṣe mọ̀ ọ́n .
Ohun to maa n je ki ibanuje yii legba kan ni pe , ko selomiran to “ mo ” omo naa to bi iya yen se mo on .
Nísisìyí nígbàtí Ámọ́nì ti
Nisisiyi nigbati Amoni ti
Ó ṣe tán , pé o gbà pé òótọ́ lára ẹ ò dá kì í ṣe àmì pé o kùnà , bó ṣe jẹ́ pé kì í ṣe ìkùnà fún atukọ̀ kan láti gbà pé òótọ́ lòún wà nínú ìjì .
O se tan , pe o gba pe ooto lara e o da ki i se ami pe o kuna , bo se je pe ki i se ikuna fun atuko kan lati gba pe ooto loun wa ninu iji .
Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká nífẹ̀ẹ́ ara wa dénú ?
Ki nidi to fi se pataki pe ka nifee ara wa denu ?
Gbogbo àwọn ará ìjọ ló ń ran Niurka lọ́wọ́ , tí wọ́n sì ń fún un níṣìírí .
Gbogbo awon ara ijo lo n ran Niurka lowo , ti won si n fun un nisiiri .
Ó bani nínú jẹ́ pé , báwọn èèyàn bá ṣàìgbọràn sí ìtọ́ni Ọlọ́run , ńṣe ni àjọṣe wọn pẹ̀lú Ọlọ́run máa ń bà jẹ́ , àpẹẹrẹ irú ìyẹn la sì rí nínú ẹgbẹ́ àlùfáà àti ọmọ ìjọ .
O bani ninu je pe , bawon eeyan ba saigboran si itoni Olorun , nse ni ajose won pelu Olorun maa n ba je , apeere iru iyen la si ri ninu egbe alufaa ati omo ijo .
Ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọdún lẹ́yìn ìgbà yẹn ni Ọlọ́run mí sí ọ̀kan lára àwọn tó kọ Sáàmù láti kọ̀wé pé : “ Àwọn olódodo ni yóò ni ilẹ̀ ayé , wọn yóò sì máa gbé títí láé lórí rẹ̀ . ”
Egbeegberun odun leyin igba yen ni Olorun mi si okan lara awon to ko Saamu lati kowe pe : " Awon olododo ni yoo ni ile aye , won yoo si maa gbe titi lae lori re . "
Pilatu bá tún wọ ààfin lọ, ó bi Jesu pé, “Ṣé ìwọ ni ọba àwọn Juu?”
Pilatu ba tun wo aafin lo, o bi Jesu pe, "Se iwo ni oba awon Juu?"
Ọ̀nà tí Jésù gbà jẹ́ ìránṣẹ́ gbogbo ènìyàn ta yọ gan - an , nítorí pé a ti fún un ní àìleèkú .
Ona ti Jesu gba je iranse gbogbo eniyan ta yo gan - an , nitori pe a ti fun un ni aileeku .
Àwọn ogun, iyapa, àtí ìwà búburú jọba láyé àwọn ara Járẹ́dì—Àwọn wòlĩ sọ àsọtẹ́lẹ̀ níti ìparun àwọn ará Járẹ́dì àfi bí wọ́n bá ronúpìwàdà—Àwọn ènìyàn nã kọ̀ ọ̀rọ̀ àwọn wòlĩ. Àwọn wòlĩ púpọ̀ sì wá pẹ̀lú ní ìgbà ayé Kọ́mù, wọ́n sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ níti ìparun àwọn ènìyàn olókìkí nnì àfi bí wọ́n bá ronúpìwàdà, kí wọn ó sì yí sí ọ́dọ́ Olúwa, kí wọn sì kọ̀ ìpànìyàn àti ìwà búburú wọn sílẹ̀.
Awon ogun, iyapa, ati iwa buburu joba laye awon ara Jaredi—Awon woli so asotele niti iparun awon ara Jaredi afi bi won ba ronupiwada—Awon eniyan na ko oro awon woli. Awon woli pupo si wa pelu ni igba aye Komu, won si so asotele niti iparun awon eniyan olokiki nni afi bi won ba ronupiwada, ki won o si yi si odo Oluwa, ki won si ko ipaniyan ati iwa buburu won sile.
Ọ̀rọ̀ sì tọ Jeremiah wá nípa àwọn ènìyàn Juda ní ọdún kẹrin Jehoiakimu ọmọ Josiah ọba Juda, èyí tí ó jẹ́ ọdún kìn-ín-ní Nebukadnessari ọba Babeli.
Oro si to Jeremiah wa nipa awon eniyan Juda ni odun kerin Jehoiakimu omo Josiah oba Juda, eyi ti o je odun kin-in-ni Nebukadnessari oba Babeli.
Ìdí nìyẹn tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi ní ẹ̀dùn ọkàn bíi ti Dáfídì , tí ìrònú wọn ò já gaara , tí wọ́n sì ń jìyà , pàápàá àwọn tó ń gbìyànjú láti múnú Ọlọ́run dùn .
Idi niyen ti opo eeyan fi ni edun okan bii ti Dafidi , ti ironu won o ja gaara , ti won si n jiya , paapaa awon to n gbiyanju lati munu Olorun dun .
Báwo ni lẹ́tà Pọ́ọ̀lù ṣe mú kí ìgbàgbọ́ Tímótì túbọ̀ lágbára ?
Bawo ni leta Poolu se mu ki igbagbo Timoti tubo lagbara ?
Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ti ń lọ sí àpéjọ ní Rọ́ṣíà fún ọ̀pọ̀ ọdún sọ pé : “ Ní àwọn ọdún tó ti kọjá , a máa ń gba àwọn pápá ìṣeré àtàwọn ilé ńlá ní àwọn ìlú ńlá , ọ̀pọ̀ àwọn olóòótọ́ ọkàn àtàwọn aláṣẹ àdúgbò ló sì má ń sọ ohun tó dára nípa ètò wa nítorí ìmọ́tótó àti ìwàlétòlétò wa tí wọ́n rí .
Elerii Jehofa kan to ti n lo si apejo ni Rosia fun opo odun so pe : “ Ni awon odun to ti koja , a maa n gba awon papa isere atawon ile nla ni awon ilu nla , opo awon oloooto okan atawon alase adugbo lo si ma n so ohun to dara nipa eto wa nitori imototo ati iwaletoleto wa ti won ri .
“ Kí ọkàn - àyà burúkú tí ó ṣaláìní ìgbàgbọ́ má bàa dìde nínú ẹnikẹ́ni nínú yín láé nípa lílọ kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run alààyè . ” — Òwe 4 : 23 ; Hébérù 3 : 12 .
" Ki okan - aya buruku ti o salaini igbagbo ma baa dide ninu enikeni ninu yin lae nipa lilo kuro lodo Olorun alaaye . " -- Owe 4 : 23 ; Heberu 3 : 12 .
Ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ti pinnu láti máa ṣe nìyẹn .
Ohun ti opo eeyan ti pinnu lati maa se niyen .