diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Òun kò gbọ́ràn sí ẹnikẹ́ni, òun kò gba ìtọ́ni, òun kò gbẹ́kẹ̀lé Olúwa , bẹ́ẹ̀ ni òun kò súnmọ́ ọ̀dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀
Oun ko gboran si enikeni, oun ko gba itoni, oun ko gbekele Oluwa , bee ni oun ko sunmo odo Olorun re
Àwọn olórí rẹ̀ jẹ́ kìnnìun tí ń ké ramúramù, àwọn onídàájọ́ rẹ̀, ìkokò àṣálẹ́ ni wọn, wọn kò sì fi nǹkan kan kalẹ̀ fún òwúrọ̀
Awon olori re je kinniun ti n ke ramuramu, awon onidaajo re, ikoko asale ni won, won ko si fi nnkan kan kale fun owuro
Àwọn wòlíì rẹ̀ gbéraga, wọ́n sì jẹ́ alárékérekè ènìyàn
Awon wolii re gberaga, won si je alarekereke eniyan
Àwọn àlùfáà rẹ̀ ti ba ibi mímọ́ jẹ́, wọ́n sì rú òfin
Awon alufaa re ti ba ibi mimo je, won si ru ofin
Olúwa ni àárin rẹ̀ jẹ́ olódodo
Oluwa ni aarin re je olododo
kì yóò ṣe ohun tí kò tọ̀nà
ki yoo se ohun ti ko tona
Àràárọ̀ ni ó máa ń mú ìdájọ́ rẹ̀ wá sí ìmọ́lẹ̀, kì í sì kùnà ní gbogbo ọjọ́ tuntun, ṣíbẹ̀ àwọn aláìsòótọ́ kò mọ ìtìjú
Araaro ni o maa n mu idajo re wa si imole, ki i si kuna ni gbogbo ojo tuntun, sibe awon alaisooto ko mo itiju
Èmi ti ké àwọn orílẹ̀-èdè kúrò, ilé gíga wọn sì ti bàjẹ́
Emi ti ke awon orile-ede kuro, ile giga won si ti baje
Mo ti fi ìgboro wọn sílẹ̀ ní ihà tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnìkan kan kò kọjá níbẹ̀
Mo ti fi igboro won sile ni iha tobee ti enikan kan ko koja nibe
Ìlú wọn parun tóbẹ́ẹ̀ tí kò sí ẹnikan tí yóò sẹ́kù, kò sì ní sí ẹnìkan rárá
Ilu won parun tobee ti ko si enikan ti yoo seku, ko si ni si enikan rara
Èmi wí fún ìlú náà wí pé Nítòótọ́, ìwọ yóò bẹ̀rù mi, ìwọ yóò sì gba ìtọ́ni! Bẹ́ẹ̀ ni, a kì yóò ké ibùgbé rẹ̀ kúrò bí ó ti wù kí ń jẹ wọ́n níyà tó
Emi wi fun ilu naa wi pe Nitooto, iwo yoo beru mi, iwo yoo si gba itoni! Bee ni, a ki yoo ke ibugbe re kuro bi o ti wu ki n je won niya to
Ṣùgbọ́n ṣíbẹ̀ wọ́n sì tún ní ìtara láti ba iṣẹ́ wọn jẹ́
Sugbon sibe won si tun ni itara lati ba ise won je
Nítorí náà ẹ dúró dèmi, ni Olúwa wí, títí di ọjọ́ náà tí èmi yóò dìde si ohun ọdẹ
Nitori naa e duro demi, ni Oluwa wi, titi di ojo naa ti emi yoo dide si ohun ode
nítorí ìpinnu mi ni láti kó orílẹ̀-èdè jọ kí èmi kí ó lè kó ilẹ̀ ọba jọ àti láti rú ìbínú jáde sórí wọn, àní gbogbo ibínú gbígbóná mi
nitori ipinnu mi ni lati ko orile-ede jo ki emi ki o le ko ile oba jo ati lati ru ibinu jade sori won, ani gbogbo ibinu gbigbona mi
Nítorí, a ó fi iná owú ibínú jẹ gbogbo ayé run
Nitori, a o fi ina owu ibinu je gbogbo aye run
Nígbà náà ni èmi yóò yí èdè àwọn ènìyàn padà sí èdè mímọ́, nítorí kí gbogbo wọn bá a lè máa pe orúkọ Olúwa , láti fi ọkàn kan sìnín
Nigba naa ni emi yoo yi ede awon eniyan pada si ede mimo, nitori ki gbogbo won ba a le maa pe oruko Oluwa , lati fi okan kan sinin
Láti òkè odò Etiópíà, àwọn olùsìn mi, àwọn ènìyàn mi tí ó ti fọ́nká, yóò mú ọrẹ wá fún mi
Lati oke odo Etiopia, awon olusin mi, awon eniyan mi ti o ti fonka, yoo mu ore wa fun mi
Ní ọjọ́ náà ni a kì yóò sì dójútì nítorí gbogbo ìsẹ́ni tí ó ti ṣe sí mi, nígbà náà ni èmi yóò mu kúrò nínú ìlú yìí, àwọn tí ń yọ̀ nínú ìgbéraga wọn
Ni ojo naa ni a ki yoo si dojuti nitori gbogbo iseni ti o ti se si mi, nigba naa ni emi yoo mu kuro ninu ilu yii, awon ti n yo ninu igberaga won
Ìwọ kì yóò sì gbéraga mọ́ ní òkè mímọ́ mi
Iwo ki yoo si gberaga mo ni oke mimo mi
Ṣùgbọ́n Èmi yóò fi àwọn ọlọ́kàn tútù àti onírẹ̀lẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ni àárin rẹ̀, wọn yóò sì gbẹ́kẹ̀lé orúkọ Olúwa
Sugbon Emi yoo fi awon olokan tutu ati onirele sile pelu ni aarin re, won yoo si gbekele oruko Oluwa
Àwọn ìyókù Ísírẹ́lì kì yóò hùwà ibi, wọn kì yóò sọ̀rọ̀ èké, bẹ́ẹ̀ ni a kì yóò rí ahọ́n àrékérekè ní ẹnu wọn
Awon iyoku Isireli ki yoo huwa ibi, won ki yoo soro eke, bee ni a ki yoo ri ahon arekereke ni enu won
Àwọn yóò jẹun, wọn yóò sì dùbúlẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kì yóò dẹ́rù bà wọ́n
Awon yoo jeun, won yoo si dubule, bee ni enikeni ki yoo deru ba won
Kọrin, ìwọ ọmọbìnrin Síónì, kígbé sókè, ìwọ Ísírẹ́lì! Fi gbogbo ọkàn yọ̀, kí inú rẹ kí ó sì dùn, ìwọ ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù
Korin, iwo omobinrin Sioni, kigbe soke, iwo Isireli! Fi gbogbo okan yo, ki inu re ki o si dun, iwo omobinrin Jerusalemu
Olúwa ti mú ìdájọ́ rẹ wọ̀n-ọn-nì kúrò, ó sì ti ti àwọn ọ̀ta rẹ padà sẹ́yìn
Oluwa ti mu idajo re won-on-ni kuro, o si ti ti awon ota re pada seyin
Olúwa , ọba Ísírẹ́lì wà pẹ̀lú rẹ, Ìwọ kì yóò sì bẹ̀rù ibi kan mọ́
Oluwa , oba Isireli wa pelu re, Iwo ki yoo si beru ibi kan mo
Ní ọjọ́ náà, wọn yóò sọ fún Jérúsálẹ́mù pé, Má ṣe bẹ̀rù Síónì
Ni ojo naa, won yoo so fun Jerusalemu pe, Ma se beru Sioni
má sì ṣe jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó dẹ̀
ma si se je ki owo re ki o de
Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ, Ó ní agbára láti gbà ọ là
Oluwa Olorun re wa pelu re, O ni agbara lati gba o la
Yóò yọ̀ ni orí rẹ fún ayọ̀
Yoo yo ni ori re fun ayo
Yóò tún ọ se nínú ìfẹ́ rẹ̀, Yóò sì fi orin yọ̀ ní orí rẹ
Yoo tun o se ninu ife re, Yoo si fi orin yo ni ori re
Èmi ó kó àwọn tí ó ń banújẹ̀ fún àjọ mímọ́ jọ, àwọn tí ó jẹ́ tirẹ̀
Emi o ko awon ti o n banuje fun ajo mimo jo, awon ti o je tire
àwọn tí ẹ̀gàn rẹ̀ jásí ẹ̀rù
awon ti egan re jasi eru
Ní àkókò náà ni èmi yóò dojúkọ àwọn tí ń ni yín lára, èmi yóò gba atiro là, èmi yóò sì ṣa àwọn tí ó ti fọ́nká jọ, èmi yóò fi ìyìn àti ọlá fún wọn ní gbogbo ilẹ̀ tí a bá ti dójútì wọ́n
Ni akoko naa ni emi yoo dojuko awon ti n ni yin lara, emi yoo gba atiro la, emi yoo si sa awon ti o ti fonka jo, emi yoo fi iyin ati ola fun won ni gbogbo ile ti a ba ti dojuti won
Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ
Ni akoko naa ni emi yoo sa yin jo
Nígbà náà ni èmi yóò mú un yín padà wá sílé
Nigba naa ni emi yoo mu un yin pada wa sile
Èmi yóò fi ọlá àti ìyìn fún un yín láàárin gbogbo ènìyàn àgbáyé, nígbà tí èmi yóò yí ìgbèkùn yín padà bọ sípò ní ojú ara yín, ni Olúwa wíNítorí pé ẹ ti gbàgbé Ọlọrun olùgbàlà yín,ẹ kò ranti Àpáta tí ó jẹ́ ààbò yín.Nítorí náà bí ẹ tilẹ̀ gbin igi dáradára tí ẹ̀ ń bọ ọ́,tí ẹ sì gbin òdòdó àjèjì tí ẹ̀ ń sìn ín;Wọ́n ní, “Ẹ̀yin ará Galili, kí ló dé tí ẹ fi dúró tí ẹ̀ ń wòkè bẹ́ẹ̀? Jesu kan náà, tí a mú kúrò lọ́dọ̀ yín, lọ sí ọ̀run yìí, yóo tún pada wá bí ẹ ṣe rí i tí ó ń lọ sí ọ̀run.”“Permit me to perch by you” takes the whole seat; the parasite becomes the host.
Emi yoo fi ola ati iyin fun un yin laaarin gbogbo eniyan agbaye, nigba ti emi yoo yi igbekun yin pada bo sipo ni oju ara yin, ni Oluwa wiNitori pe e ti gbagbe Olorun olugbala yin,e ko ranti Apata ti o je aabo yin.Nitori naa bi e tile gbin igi daradara ti e n bo o,ti e si gbin ododo ajeji ti e n sin in;Won ni, “Eyin ara Galili, ki lo de ti e fi duro ti e n woke bee? Jesu kan naa, ti a mu kuro lodo yin, lo si orun yii, yoo tun pada wa bi e se ri i ti o n lo si orun.”“Permit me to perch by you” takes the whole seat; the parasite becomes the host.
Kí Oluwa alaafia fúnrarẹ̀ fun yín ní alaafia nígbà gbogbo lọ́nà gbogbo. Kí Oluwa wà pẹlu gbogbo yín.tí ó ní, “N kò ní wọ inú ilé mi,bẹ́ẹ̀ ni n kò ní bọ́ sí orí ibùsùn mi;Ohun tí OLUWA sọ fún wolii Jeremaya nípa Nebukadinesari, ọba Babiloni nígbà tí ó ń bọ̀ wá ṣẹgun ilẹ̀ Ijipti nìyí: OLUWA bá dá a lóhùn pé, “Ojú mi yóo máa bá ọ lọ, n óo sì fún ọ ní ìsinmi.”OLUWA bá pe Samuẹli, ó ní, “Samuẹli! Samuẹli!” Samuẹli dáhùn pé, “Èmi nìyí.” Mose fún àwọn ẹ̀yà Reubẹni ní ilẹ̀, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn. “Nígbà tí ẹ bá rú ẹbọ alaafia sí OLUWA, ẹ rú u ní ọ̀nà tí yóo fi jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà. Ìtórò tó so lóko tí kò fẹ̀hìntì, afẹ́fẹ́ oko ní ńtú u.
Ki Oluwa alaafia funrare fun yin ni alaafia nigba gbogbo lona gbogbo. Ki Oluwa wa pelu gbogbo yin.ti o ni, “N ko ni wo inu ile mi,bee ni n ko ni bo si ori ibusun mi;Ohun ti OLUWA so fun wolii Jeremaya nipa Nebukadinesari, oba Babiloni nigba ti o n bo wa segun ile Ijipti niyi: OLUWA ba da a lohun pe, “Oju mi yoo maa ba o lo, n oo si fun o ni isinmi.”OLUWA ba pe Samueli, o ni, “Samueli! Samueli!” Samueli dahun pe, “Emi niyi.” Mose fun awon eya Reubeni ni ile, gege bi iye idile won. “Nigba ti e ba ru ebo alaafia si OLUWA, e ru u ni ona ti yoo fi je itewogba. Itoro to so loko ti ko fehinti, afefe oko ni ntu u.
Ọ̀rọ̀ àwọn eniyan burúkú dàbí ẹni tí ó lúgọ láti pa eniyan,ṣugbọn ọ̀rọ̀ ẹnu olódodo a máa gbani là.Bí ẹ̀yin fúnra yín ti jẹ́ aláìgbọràn sí Ọlọrun nígbà kan rí, ṣugbọn tí ó wá ṣàánú yín nígbà tí àwọn Juu ṣàìgbọràn, Kí ló tún kù! Gbogbo àwọn iranṣẹ ọba ni wọ́n ti lọ kí Dafidi ọba, pé, ‘Kí Ọlọrun rẹ mú kí Solomoni lókìkí jù ọ́ lọ, kí ìjọba rẹ̀ sì ju tìrẹ lọ.’ Ọba bá tẹríba, ó sì sin Ọlọrun lórí ibùsùn rẹ̀, Ní àkókò náà, ọkunrin kan láti inú ẹ̀yà Lefi fẹ́ obinrin kan tí òun náà jẹ́ ẹ̀yà Lefi. Ó ní, “Ọlọrun ti fi ẹ̀bùn rere fún mi, nígbà yìí ni ọkọ mi yóo tó bu ọlá fún mi, nítorí pé mo bí ọkunrin mẹfa fún un,” nítorí náà ó sọ ọmọ náà ní Sebuluni. OLUWA pàṣẹ fún Mose pé kí ó bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu mìíràn ní ilẹ̀ Moabu, yàtọ̀ sí èyí tí ó ti bá wọn dá ní òkè Horebu.Nígbà tí Reubẹni pada dé ibi kànga gbígbẹ tí wọ́n ju Josẹfu sí, tí ó rí i pé kò sí níbẹ̀ mọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn. Nítorí pé OLUWA sọ̀rọ̀, ayé wà;ó pàṣẹ, ayé sì dúró.The kite watches the monkey but has no hands to carry it off.
Oro awon eniyan buruku dabi eni ti o lugo lati pa eniyan,sugbon oro enu olododo a maa gbani la.Bi eyin funra yin ti je alaigboran si Olorun nigba kan ri, sugbon ti o wa saanu yin nigba ti awon Juu saigboran, Ki lo tun ku! Gbogbo awon iranse oba ni won ti lo ki Dafidi oba, pe, ‘Ki Olorun re mu ki Solomoni lokiki ju o lo, ki ijoba re si ju tire lo.’ Oba ba teriba, o si sin Olorun lori ibusun re, Ni akoko naa, okunrin kan lati inu eya Lefi fe obinrin kan ti oun naa je eya Lefi. O ni, “Olorun ti fi ebun rere fun mi, nigba yii ni oko mi yoo to bu ola fun mi, nitori pe mo bi okunrin mefa fun un,” nitori naa o so omo naa ni Sebuluni. OLUWA pase fun Mose pe ki o ba awon omo Israeli da majemu miiran ni ile Moabu, yato si eyi ti o ti ba won da ni oke Horebu.Nigba ti Reubeni pada de ibi kanga gbigbe ti won ju Josefu si, ti o ri i pe ko si nibe mo, o fa aso re ya lati fi ibanuje re han. Nitori pe OLUWA soro, aye wa;o pase, aye si duro.The kite watches the monkey but has no hands to carry it off.
Hẹrọdu bá pe àwọn amòye náà síkọ̀kọ̀, ó fọgbọ́n wádìí àkókò tí ìràwọ̀ náà yọ lọ́dọ̀ wọn. Òkò àbínújù kì í pẹyẹ.
Herodu ba pe awon amoye naa sikoko, o fogbon wadii akoko ti irawo naa yo lodo won. Oko abinuju ki i peye.
Nítorí náà, ẹ fi èké ṣíṣe sílẹ̀. Kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín máa bá ẹnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́, nítorí gbogbo wa jẹ́ ẹ̀yà ara kan náà. Àwọn ọmọ Merari gba ìlú mejila lọ́wọ́ àwọn ẹ̀yà Reubẹni, ẹ̀yà Gadi ati ẹ̀yà Sebuluni.Solomoni fi ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbaa (22,000) mààlúù, ati ọ̀kẹ́ mẹfa (120,000) aguntan rú ẹbọ alaafia sí OLUWA. Bẹ́ẹ̀ ni òun ati àwọn ọmọ Israẹli ṣe ya ilé OLUWA náà sí mímọ́. He entered through the front door, but it was through a hidden shortcut that he snuck away; it consulted the Ifa oracle for the visitor who has an affair with his host's wife.
Nitori naa, e fi eke sise sile. Ki enikookan yin maa ba enikeji re so otito, nitori gbogbo wa je eya ara kan naa. Awon omo Merari gba ilu mejila lowo awon eya Reubeni, eya Gadi ati eya Sebuluni.Solomoni fi oke kan ati egbaa (22,000) maaluu, ati oke mefa (120,000) aguntan ru ebo alaafia si OLUWA. Bee ni oun ati awon omo Israeli se ya ile OLUWA naa si mimo. He entered through the front door, but it was through a hidden shortcut that he snuck away; it consulted the Ifa oracle for the visitor who has an affair with his host's wife.
Whoever abuses his hospitality will depart with disgrace. The formulation is typical of several in which a leading statement describing a situation is followed by the statement, “Ó dÍfá fún” (He consulted the Ifa oracle for), and then followed by a description of the behavior that leads to the condition described at the opening.
Whoever abuses his hospitality will depart with disgrace. The formulation is typical of several in which a leading statement describing a situation is followed by the statement, “O dIfa fun” (He consulted the Ifa oracle for), and then followed by a description of the behavior that leads to the condition described at the opening.
Ninu ọpọlọpọ òwò tí ó ń ṣe, o bẹ̀rẹ̀ sí hu ìwà jàgídíjàgan, o sì dẹ́ṣẹ̀, nítorí náà mo lé ọ jáde bí ohun ìríra kúrò lórí òkè Ọlọrun. Kerubu tí ń ṣọ́ ọ sì lé ọ jáde kúrò láàrin àwọn òkúta olówó iyebíye tí ń tàn yinrinyinrin. Agbára OLUWA sọ̀kalẹ̀ sórí Elija, ó di àmùrè rẹ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí sáré lọ; ó sì ṣáájú Ahabu dé ẹnubodè Jesireeli.Nítorí gbogbo àwọn yòókù mú ọrẹ wá ninu ọ̀pọ̀ ohun tí wọ́n ní; ṣugbọn òun tí ó jẹ́ aláìní, ó mú gbogbo ohun tí ó fi ẹ̀mí tẹ̀ wá.”Rárá o! Bí Ọlọrun kò bá ní ẹ̀tọ́ láti bínú, báwo ni yóo ṣe wá ṣe ìdájọ́ aráyé?Whatever sent the brown monkey climbing to the top of the thorny acacia tree: unless it sees something even more terrifying it will not climb down.
Ninu opolopo owo ti o n se, o bere si hu iwa jagidijagan, o si dese, nitori naa mo le o jade bi ohun irira kuro lori oke Olorun. Kerubu ti n so o si le o jade kuro laarin awon okuta olowo iyebiye ti n tan yinrinyinrin. Agbara OLUWA sokale sori Elija, o di amure re mo egbe, o bere si sare lo; o si saaju Ahabu de enubode Jesireeli.Nitori gbogbo awon yooku mu ore wa ninu opo ohun ti won ni; sugbon oun ti o je alaini, o mu gbogbo ohun ti o fi emi te wa.”Rara o! Bi Olorun ko ba ni eto lati binu, bawo ni yoo se wa se idajo araye?Whatever sent the brown monkey climbing to the top of the thorny acacia tree: unless it sees something even more terrifying it will not climb down.
A tún rí ẹ̀rí tí ó dájú ninu àsọtẹ́lẹ̀ àwọn wolii, pé, kí ẹ ṣe akiyesi ọ̀rọ̀ yìí, nítorí ó dàbí fìtílà tí ń tàn ninu òkùnkùn, títí ilẹ̀ yóo fi mọ̀, títí ìràwọ̀ òwúrọ̀ yóo fi tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ sinu ọkàn yín. Ó tẹ́ ẹ sí inú ibojì rẹ̀ titun tí òun tìkalárarẹ̀ ti gbẹ́ sí inú àpáta. Ó yí òkúta ńlá kan dí ẹnu ọ̀nà ibojì náà. Ó bá kúrò níbẹ̀. Ohun tí yóo kù ninu àwọn igi igbó rẹ̀kò ní ju ohun tí ọmọde lè kà, kí ó sì kọ sílẹ̀ lọ.Mose bá gòkè tọ Ọlọrun lọ.OLUWA pè é láti orí òkè náà, ó ní, “Ohun tí mo fẹ́ kí o sọ fún àwọn ọmọ Israẹli nìyí, Filipi bá tẹnu bọ ọ̀rọ̀. Ó bẹ̀rẹ̀ láti ibi àkọsílẹ̀ yìí, ó waasu ìyìn rere Jesu fún un. Ṣugbọn láàyè ni yóo fa ẹran tí gègé Asaseli bá mú kalẹ̀ níwájú OLUWA, yóo ṣe ètùtù lórí rẹ̀, yóo sì tú u sílẹ̀, kí ó sá tọ Asaseli lọ ninu aṣálẹ̀.Lákòókò náà gan-an ni àwọn ọkunrin mẹta tí a rán sí mi láti Kesaria dé ilé tí mo wà. Lẹ́yìn náà Ọlọrun wí fún obinrin náà pé,“N óo fi kún ìnira rẹ nígbà tí o bá lóyún,ninu ìrora ni o óo máa bímọ.Sibẹsibẹ, lọ́dọ̀ ọkọ rẹ ni ìfẹ́ rẹ yóo máa fà sí,òun ni yóo sì máa ṣe olórí rẹ.”Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọrun a óo ṣe akin,nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.Ní ọjọ́ náà, n óo fi ìwọ Serubabeli, ọmọ Ṣealitieli, ṣe aṣojú ninu ìjọba mi nítorí pé mo ti yàn ọ́. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.”The Akee apple is never so blighted that one does not find a seed in it.
A tun ri eri ti o daju ninu asotele awon wolii, pe, ki e se akiyesi oro yii, nitori o dabi fitila ti n tan ninu okunkun, titi ile yoo fi mo, titi irawo owuro yoo fi tan imole re sinu okan yin. O te e si inu iboji re titun ti oun tikalarare ti gbe si inu apata. O yi okuta nla kan di enu ona iboji naa. O ba kuro nibe. Ohun ti yoo ku ninu awon igi igbo reko ni ju ohun ti omode le ka, ki o si ko sile lo.Mose ba goke to Olorun lo.OLUWA pe e lati ori oke naa, o ni, “Ohun ti mo fe ki o so fun awon omo Israeli niyi, Filipi ba tenu bo oro. O bere lati ibi akosile yii, o waasu iyin rere Jesu fun un. Sugbon laaye ni yoo fa eran ti gege Asaseli ba mu kale niwaju OLUWA, yoo se etutu lori re, yoo si tu u sile, ki o sa to Asaseli lo ninu asale.Lakooko naa gan-an ni awon okunrin meta ti a ran si mi lati Kesaria de ile ti mo wa. Leyin naa Olorun wi fun obinrin naa pe,“N oo fi kun inira re nigba ti o ba loyun,ninu irora ni o oo maa bimo.Sibesibe, lodo oko re ni ife re yoo maa fa si,oun ni yoo si maa se olori re.”Pelu atileyin Olorun a oo se akin,nitori oun ni yoo te awon ota wa mole.Ni ojo naa, n oo fi iwo Serubabeli, omo Sealitieli, se asoju ninu ijoba mi nitori pe mo ti yan o. Bee ni emi OLUWA awon omo ogun wi.”The Akee apple is never so blighted that one does not find a seed in it.
Nítorí pé, a óo yọ àwọn tí wọ́n bá ṣe àwọn ohun ìríra kúrò láàrin àwọn eniyan wọn.Ọba Babiloni kó gbogbo ohun èlò ilé OLUWA, ati ńláńlá, ati kéékèèké, ati àwọn ìṣúra tí ó wà níbẹ̀, ati àwọn tí wọ́n wà ní ààfin ati ti ilé àwọn ìjòyè; ó kó gbogbo wọn patapata lọ sí Babiloni. Mo bi í pé, “Níbo ni ò ń lọ?” Ó bá dáhùn pé, “Mò ń lọ wọn Jerusalẹmu, kí n lè mọ òòró ati ìbú rẹ̀ ni.”O kò ní ipa tabi ìpín ninu ọ̀rọ̀ yìí, nítorí ọkàn rẹ kò tọ́ níwájú Ọlọrun. “Nítorí náà, kọ orin yìí sílẹ̀ nisinsinyii kí o sì kọ́ àwọn ọmọ Israẹli, kí orin náà lè jẹ́ ẹlẹ́rìí mi lọ́dọ̀ wọn. Joṣua bá pe àwọn ọkunrin mejila tí ó ti yàn tẹ́lẹ̀ ninu àwọn ọmọ Israẹli, ẹnìkọ̀ọ̀kan láti inú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan; Àro stayed so long on the farm that he forgot how to beat the drum.
Nitori pe, a oo yo awon ti won ba se awon ohun irira kuro laarin awon eniyan won.Oba Babiloni ko gbogbo ohun elo ile OLUWA, ati nlanla, ati keekeeke, ati awon isura ti o wa nibe, ati awon ti won wa ni aafin ati ti ile awon ijoye; o ko gbogbo won patapata lo si Babiloni. Mo bi i pe, “Nibo ni o n lo?” O ba dahun pe, “Mo n lo won Jerusalemu, ki n le mo ooro ati ibu re ni.”O ko ni ipa tabi ipin ninu oro yii, nitori okan re ko to niwaju Olorun. “Nitori naa, ko orin yii sile nisinsinyii ki o si ko awon omo Israeli, ki orin naa le je elerii mi lodo won. Josua ba pe awon okunrin mejila ti o ti yan tele ninu awon omo Israeli, enikookan lati inu eya kookan; Aro stayed so long on the farm that he forgot how to beat the drum.
If one neglects one's specialty long enough, one becomes incompetent at it. Àro is one of the titles of the secret order of Ògbóni; the proverb suggests that the member, from lack of practice, has forgotten the funerary rites of the order.
If one neglects one's specialty long enough, one becomes incompetent at it. Aro is one of the titles of the secret order of Ogboni; the proverb suggests that the member, from lack of practice, has forgotten the funerary rites of the order.
Ojú ní ńkán ọkọlóbìnrin; àlè méjì á jà dandan.
Oju ni nkan okolobinrin; ale meji a ja dandan.
Yóo ranti gbogbo ẹbọ ọrẹ rẹ,yóo sì gba ẹbọ sísun rẹ.Ẹ níláti mú gbogbo inú burúkú, ìrúnú, ibinu, ariwo ati ìsọkúsọ kúrò láàrin yín ati gbogbo nǹkan burúkú. Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni ó ní ìmísí Ọlọrun, ó sì wúlò fún ẹ̀kọ́, fún ìbáwí, fún ìtọ́nisọ́nà, fún ìlànà nípa ìwà òdodo, Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé lojoojumọ ni ó ń rọ Josẹfu, sibẹsibẹ, Josẹfu kò gbà láti bá a lòpọ̀, tabi láti wà pẹlu rẹ̀.Lẹ́yìn náà, Ṣalimaneseri, ọba Asiria, gbógun ti ilẹ̀ Israẹli, ó dó ti Samaria fún ọdún mẹta. Jesu dá a lóhùn pé, “Fi í sílẹ̀! Jẹ́ kí ó fi pamọ́ di ọjọ́ ìsìnkú mi. Ọmọ onílẹ̀ á tẹ̀ ẹ́ jẹ́jẹ́.
Yoo ranti gbogbo ebo ore re,yoo si gba ebo sisun re.E nilati mu gbogbo inu buruku, irunu, ibinu, ariwo ati isokuso kuro laarin yin ati gbogbo nnkan buruku. Gbogbo Iwe Mimo ni o ni imisi Olorun, o si wulo fun eko, fun ibawi, fun itonisona, fun ilana nipa iwa ododo, Bi o tile je pe lojoojumo ni o n ro Josefu, sibesibe, Josefu ko gba lati ba a lopo, tabi lati wa pelu re.Leyin naa, Salimaneseri, oba Asiria, gbogun ti ile Israeli, o do ti Samaria fun odun meta. Jesu da a lohun pe, “Fi i sile! Je ki o fi pamo di ojo isinku mi. Omo onile a te e jeje.
“Nípa èmi nìkan ni àwọn eniyan yóo máa pé,‘Ninu OLUWA ni òdodo ati agbára wà.’Gbogbo àwọn tí ń bá a bínúyóo pada wá sọ́dọ̀ rẹ̀ pẹlu ìtìjú.Iná tó ńlérí omi á kù sọnù.
“Nipa emi nikan ni awon eniyan yoo maa pe,‘Ninu OLUWA ni ododo ati agbara wa.’Gbogbo awon ti n ba a binuyoo pada wa sodo re pelu itiju.Ina to nleri omi a ku sonu.
Labani bá dá a lóhùn pé, “Ó dára, ohun tí o wí gan-an ni a óo ṣe.” Solomoni ọba bá ranṣẹ lọ mú Adonija wá láti ibi pẹpẹ. Adonija lọ siwaju ọba, ó sì wólẹ̀. Ọba sọ fún un pé kí ó máa lọ sí ilé rẹ̀.Ìwọ tí ó jẹ́ bí ẹ̀ka igi olifi tí ó la ilẹ̀ hù ninu ìgbẹ́, tí a lọ́ mọ́ ara igi olifi inú oko, tí ẹ̀dá wọn yàtọ̀ sí ara wọn, báwo ni yóo ti rọrùn tó láti tún lọ́ àwọn tí ó jẹ́ ara igi olifi inú oko tẹ́lẹ̀ mọ́ ara igi tí a ti gé wọn kúrò!Nígbà náà ni ọrùn mi yóo tó mọ́ kúrò ninu ìbúra tí mo bú fún òun. Bí mo bá dé ọ̀dọ̀ àwọn ìbátan òun, tí wọ́n bá kọ̀, tí wọn kò jẹ́ kí ọmọbinrin wọn bá mi wá, ọrùn mi yóo mọ́ kúrò ninu ìbúra tí mo bú.’Ẹ ṣí fìlà, kí ẹ sì ṣí adé ọba kúrò lórí, gbogbo nǹkan kò ní wà bí wọ́n ṣe rí. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Ẹ gbé àwọn tí ipò wọn rẹlẹ̀ ga, kí ẹ sì rẹ àwọn tí ipò wọn wà lókè sílẹ̀. Àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ̀ yóo jogún rẹ̀;àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ̀ yóo sì máa gbé inú rẹ̀.Bí ó ti fẹ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó ní, “N óo tún pada wá sí ọ̀dọ̀ yín bí Ọlọrun bá fẹ́.” Ó bá kúrò ní Efesu.láti inú ẹ̀yà Aṣeri, ó rán Seturu, ọmọ Mikaeli; Ẹ rí i pé ó ṣe olóòótọ́ sí Ọlọrun tí ó yàn án gẹ́gẹ́ bí Mose ti ṣe oloòótọ́ ninu gbogbo ìdílé Ọlọrun. nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.Nígbà tí ẹ̀ṣẹ̀ wa bá borí wa,ìwọ a máa dáríjì wá.Hesekaya bá pàṣẹ pé kí wọ́n tọ́jú àwọn yàrá tó wà ninu ilé OLUWA, wọ́n bá ṣe ìtọ́jú wọn. Àwọn alufaa dúró ní ipò wọn, àwọn ọmọ Lefi náà dúró láti kọrin sí OLUWA pẹlu ohun èlò orin tí Dafidi ṣe ati ìlànà tí ó fi lélẹ̀ láti máa fi kọrin ọpẹ́ sí OLUWA pé, “Ìfẹ́ rẹ̀ tí kìí yẹ̀ wà títí lae;” ní gbogbo ìgbà tí Dafidi bá lò wọ́n láti kọrin ìyìn. Àwọn alufaa yóo máa fọn fèrè gbogbo eniyan yóo sì dìde dúró. It-is-not-begging-and-it-is-not-stealing who whistles as he harvests corn ears; if he does not come upon me it becomes stealing; if he comes upon me it becomes “the action of” a member of the household.
Labani ba da a lohun pe, “O dara, ohun ti o wi gan-an ni a oo se.” Solomoni oba ba ranse lo mu Adonija wa lati ibi pepe. Adonija lo siwaju oba, o si wole. Oba so fun un pe ki o maa lo si ile re.Iwo ti o je bi eka igi olifi ti o la ile hu ninu igbe, ti a lo mo ara igi olifi inu oko, ti eda won yato si ara won, bawo ni yoo ti rorun to lati tun lo awon ti o je ara igi olifi inu oko tele mo ara igi ti a ti ge won kuro!Nigba naa ni orun mi yoo to mo kuro ninu ibura ti mo bu fun oun. Bi mo ba de odo awon ibatan oun, ti won ba ko, ti won ko je ki omobinrin won ba mi wa, orun mi yoo mo kuro ninu ibura ti mo bu.’E si fila, ki e si si ade oba kuro lori, gbogbo nnkan ko ni wa bi won se ri. Emi OLUWA Olorun ni mo so bee. E gbe awon ti ipo won rele ga, ki e si re awon ti ipo won wa loke sile. Awon omo awon iranse re yoo jogun re;awon ti o feran oruko re yoo si maa gbe inu re.Bi o ti fe kuro lodo won, o ni, “N oo tun pada wa si odo yin bi Olorun ba fe.” O ba kuro ni Efesu.lati inu eya Aseri, o ran Seturu, omo Mikaeli; E ri i pe o se oloooto si Olorun ti o yan an gege bi Mose ti se oloooto ninu gbogbo idile Olorun. nitori ese won.Nigba ti ese wa ba bori wa,iwo a maa dariji wa.Hesekaya ba pase pe ki won toju awon yara to wa ninu ile OLUWA, won ba se itoju won. Awon alufaa duro ni ipo won, awon omo Lefi naa duro lati korin si OLUWA pelu ohun elo orin ti Dafidi se ati ilana ti o fi lele lati maa fi korin ope si OLUWA pe, “Ife re ti kii ye wa titi lae;” ni gbogbo igba ti Dafidi ba lo won lati korin iyin. Awon alufaa yoo maa fon fere gbogbo eniyan yoo si dide duro. It-is-not-begging-and-it-is-not-stealing who whistles as he harvests corn ears; if he does not come upon me it becomes stealing; if he comes upon me it becomes “the action of” a member of the household.
Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli bá parapọ̀, wọ́n wá sọ́dọ̀ Dafidi ní Heburoni, wọ́n ní, “Wò ó, ẹ̀jẹ̀ kan náà ni gbogbo wa pẹlu rẹ. OLUWA, ìwọ ni Ọlọrun mi.N óo gbé ọ ga:n óo yin orúkọ rẹ.Nítorí pé o ti ṣe àwọn nǹkan ìyanu,o ti ṣe àwọn ètò láti ìgbà àtijọ́,o mú wọn ṣẹ pẹlu òtítọ́.A kọ orúkọ àwọn ọmọ Israẹli sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìran wọn; a kọ wọ́n sinu ìwé Àwọn Ọba Israẹli.A kó àwọn ẹ̀yà Juda ní ìgbèkùn lọ sí Babiloni nítorí pé wọ́n ṣe alaiṣootọ sí Ọlọrun. Nítorí náà, ẹ máa ṣọ́ra. Ẹ ranti pé fún ọdún mẹta, tọ̀sán-tòru ni n kò fi sinmi láti máa gba ẹnìkọ̀ọ̀kan yín níyànjú pẹlu omi lójú.“Gbogbo ìdámẹ́wàá ilẹ̀ náà, kì báà jẹ́ ti èso ilẹ̀, tabi ti èso igi, ti OLUWA ni; mímọ́ ni fún OLUWA. Gbogbo èyí rí bẹ́ẹ̀ kí Ìwé Mímọ́ lè ṣẹ tí ó wí pé, “Kò sí egungun rẹ̀ kan tí wọ́n ṣẹ́.” A mọ odi náà parí ní ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù Eluli. Ó gbà wá ní ọjọ́ mejilelaadọta. OLUWA níí gbani,kí ibukun rẹ̀ kí ó wà lórí àwọn eniyan rẹ̀.41. Njẹ, nígbà náà, ìwọ ha lẹ̀ mú
Gbogbo awon omo Israeli ba parapo, won wa sodo Dafidi ni Heburoni, won ni, “Wo o, eje kan naa ni gbogbo wa pelu re. OLUWA, iwo ni Olorun mi.N oo gbe o ga:n oo yin oruko re.Nitori pe o ti se awon nnkan iyanu,o ti se awon eto lati igba atijo,o mu won se pelu otito.A ko oruko awon omo Israeli sile gege bi iran won; a ko won sinu iwe Awon Oba Israeli.A ko awon eya Juda ni igbekun lo si Babiloni nitori pe won se alaisooto si Olorun. Nitori naa, e maa sora. E ranti pe fun odun meta, tosan-toru ni n ko fi sinmi lati maa gba enikookan yin niyanju pelu omi loju.“Gbogbo idamewaa ile naa, ki baa je ti eso ile, tabi ti eso igi, ti OLUWA ni; mimo ni fun OLUWA. Gbogbo eyi ri bee ki Iwe Mimo le se ti o wi pe, “Ko si egungun re kan ti won se.” A mo odi naa pari ni ojo keedogbon osu Eluli. O gba wa ni ojo mejilelaadota. OLUWA nii gbani,ki ibukun re ki o wa lori awon eniyan re.41. Nje, nigba naa, iwo ha le mu
kí adití gbọrọ, tàbí kí o fi ònà mọ
ki aditi gboro, tabi ki o fi ona mo
afọjú àti ẹni t0 n bẹ nínú ìṣìnà tú
afoju ati eni t0 n be ninu isina tu
hàn gbangba?
han gbangba?
42. Bí A bá mú ọ kúrò, sìbẹ̀síbẹ̀
42. Bi A ba mu o kuro, sibesibe
Awa yòò gbẹ̀san lára wọn,
Awa yoo gbesan lara won,
43. Tàbí kí A fi ohun tí A ṣe ìlérí
43. Tabi ki A fi ohun ti A se ileri
rẹ̀ fún wọn hàn ọ; nítorí pé Awa
re fun won han o; nitori pe Awa
Jẹ Alágbára lòrí wọn.
Je Alagbara lori won.
44. Nítorí náà, di ohun tí A
44. Nitori naa, di ohun ti A
ṣípayá fún ọ mú ṣinṣin. Dájúdájú
sipaya fun o mu sinsin. Dajudaju
ìwọ wà ní ojú ọnà tààrà.
iwo wa ni oju ona taara.
45. Nítòòtọ, Òô jẹ ìrántí tô ga fún ọ
45. Nitooto, Oo je iranti to ga fun o
àti àwọn ẹ̀nìyàn rẹ; àti pẹ̀ a ô bi
ati awon eniyan re; ati pe a o bi
yin léẹ̀rẹ̀ (nípa rẹ̀).
yin leere (nipa re).
46. Kí o sì bẹ̀ẹ̀rò lọwọ àwọn òjíṣẹ
46. Ki o si beero lowo awon ojise
Wa tí A rán síwájú rẹ pé, 'Njẹ
Wa ti A ran siwaju re pe, 'Nje
Awa ha yan àwọn ọlọrun mìíràn
Awa ha yan awon olorun miiran
yàtọ sí Ọba Oníkẹ̀ẹ tí wọn yòò
yato si Oba Onikee ti won yoo
máa sìn bí?
maa sin bi?
ÌDÁ 5
IDA 5
47. Nítòòtọ Àwá rán Musa pẹ̀lú
47. Nitooto Awa ran Musa pelu
àwọn Amì Wa sí Fir'aona àti
awon Ami Wa si Fir'aona ati
àwọn ìjòyẹ̀ rẹ̀, 0 sì wí pé, 'Nítòôtọ,
awon ijoye re, 0 si wi pe, 'Nitooto,
Emí jẹ̀ òjíṣẹ láti òdọ. Olúwa
Emi je ojise lati odo. Oluwa
gbogbo ayé .
gbogbo aye .
48. Ṣùgbọn nígbà ti o de ọdọ wọn
48. Sugbon nigba ti o de odo won
pẹ̀lú àwọn Amì Wa, kíyẹ̀si i, wọn
pelu awon Ami Wa, kiyesi i, won
fi wỌn rẹrìn-ín.
fi wOn rerin-in.
49. Àwa kò fi Àmì kan hàn wòn
49. Awa ko fi Ami kan han won
àyàfì ẹ̀yí tO tQbi ju irú rẹ̀ tí a ti
ayafi eyi tO tQbi ju iru re ti a ti
fihàn níṣaájú, Awá sì gbá wọn mú
fihan nisaaju, Awa si gba won mu
pẹ̀lú ìjìyà Wa kí wọn lẹ̀ ṣẹrí padà
pelu ijiya Wa ki won le seri pada
Sibẹ wọn kò gbọ́ tèmi, wọn kò tẹ́tí sí mi. Kàkà bẹ́ẹ̀, oríkunkun ni wọ́n ń ṣe. Iṣẹ́ burúkú wọn ju ti àwọn baba ńlá wọn lọ.Bí angẹli tí ó ń bá a sọ̀rọ̀ ti lọ tán, ó pe meji ninu àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati ọmọ-ogun olùfọkànsìn kan, ọ̀kan ninu àwọn tí ó máa ń dúró tì í tímọ́tímọ́. Bí Ọlọrun bá gba ẹ̀mí rẹ̀ sọ́dọ̀ ara rẹ̀,tí ó sì gba èémí rẹ̀ pada sọ́dọ̀,nítorí ó wí pé:“Ṣebí ọba ni gbogbo àwọn olórí ogun mi!Harimu, Seorimu; Agbọ́tí bá rọ́ àlá tirẹ̀ fún Josẹfu, ó ní, “Mo rí ìtàkùn àjàrà kan lójú àlá. Bí a bá gba gbogbo ohun tí wọ́n fẹ̀mí tẹ̀,ṣé wọn kò ní kú bí aláìgbọ́n?’ Dìde, tan ìmọ́lẹ̀; nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé,ògo OLUWA sì ti tàn sára rẹ.“Ṣugbọn àwọn eniyan mi kò gbọ́ràn sí mi lẹ́nu,Israẹli kò sì gba tèmi.Ẹgbẹ́ ẹni kì í wọ́n láyé ká wá a lọ sọ́run.
Sibe won ko gbo temi, won ko teti si mi. Kaka bee, orikunkun ni won n se. Ise buruku won ju ti awon baba nla won lo.Bi angeli ti o n ba a soro ti lo tan, o pe meji ninu awon iranse re ati omo-ogun olufokansin kan, okan ninu awon ti o maa n duro ti i timotimo. Bi Olorun ba gba emi re sodo ara re,ti o si gba eemi re pada sodo,nitori o wi pe:“Sebi oba ni gbogbo awon olori ogun mi!Harimu, Seorimu; Agboti ba ro ala tire fun Josefu, o ni, “Mo ri itakun ajara kan loju ala. Bi a ba gba gbogbo ohun ti won femi te,se won ko ni ku bi alaigbon?’ Dide, tan imole; nitori imole re ti de,ogo OLUWA si ti tan sara re.“Sugbon awon eniyan mi ko gboran si mi lenu,Israeli ko si gba temi.Egbe eni ki i won laye ka wa a lo sorun.
Alágbàṣe tí kì í ṣe olùṣọ́-aguntan, tí kì í sìí ṣe olówó aguntan, bí ó bá rí ìkookò tí ń bọ̀, a fi àwọn aguntan sílẹ̀, a sálọ. Ìkookò a gbé ninu àwọn aguntan lọ, a sì tú wọn ká, The chicken that shits and does not piss retains the rest in its body.
Alagbase ti ki i se oluso-aguntan, ti ki i sii se olowo aguntan, bi o ba ri ikooko ti n bo, a fi awon aguntan sile, a salo. Ikooko a gbe ninu awon aguntan lo, a si tu won ka, The chicken that shits and does not piss retains the rest in its body.
Jesu mọ ohun tí wọn ń rò lọ́kàn. Ó bá mú ọmọde kan, ó gbé e dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀. N óo mú gbogbo ọ̀rọ̀ burúkú tí mo ti sọ nípa ilẹ̀ náà ṣẹ, ati gbogbo ohun tí a kọ sinu ìwé yìí, àní àwọn àsọtẹ́lẹ̀ tí Jeremaya sọ nípa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè. àwọn arọmọdọmọ wọn Jẹ Yahudi
Jesu mo ohun ti won n ro lokan. O ba mu omode kan, o gbe e duro legbee re. N oo mu gbogbo oro buruku ti mo ti so nipa ile naa se, ati gbogbo ohun ti a ko sinu iwe yii, ani awon asotele ti Jeremaya so nipa gbogbo awon orile-ede. awon aromodomo won Je Yahudi
(Juu) tàbí Nasara. (Kirisitiẹni)
(Juu) tabi Nasara. (Kirisitieni)
bí? wí pé, 'N jẹ ẹ̀yin ni ẹ mò jù
bi? wi pe, 'N je eyin ni e mo ju
ni tàbí Allah?" Ta sì ni ẹni tí O jẹ̀
ni tabi Allah?" Ta si ni eni ti O je
alábòsí ju ẹni tí Òô fi ẹ̀rí tò ní láti
alabosi ju eni ti Oo fi eri to ni lati
òdò Allah pamọ. Allah kò ṣàì
odo Allah pamo. Allah ko sai
kọbiara sí ohun tí ẹ̀ n ṣe.
kobiara si ohun ti e n se.
142. Àwọn wọnyí ni ìjọ ẹ̀nìyàn tÔ
142. Awon wonyi ni ijo eniyan tO
ti kọjá lọ, ẹ̀san iṣẹ wọn n. bẹ fún
ti koja lo, esan ise won n. be fun
wọn, bẹ̀ẹ̀ ni ẹ̀san iṣẹ yín sì n bẹ
won, bee ni esan ise yin si n be
fún yín, A kì yòò sì bi yín léẹ̀rẹ̀,
fun yin, A ki yoo si bi yin leere,
nípa ohun tí wọn ti ṣe.
nipa ohun ti won ti se.
ÌPIN2
IPIN2
ÌDÁ 17
IDA 17
143. Àwọn òmùgọ nínú àwọn
143. Awon omugo ninu awon
ẹ̀nìyàn yòò sọ pé kí lô yí wọn
eniyan yoo so pe ki lo yi won