diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Nítorí náà , òótọ́ ni pé níní ìmọ̀ àwọn èdè àtijọ́ lè wúlò nígbà mìíràn , síbẹ̀ kò pọn dandan .
Nitori naa , ooto ni pe nini imo awon ede atijo le wulo nigba miiran , sibe ko pon dandan .
Ará, ohun tí mò ń sọ ni pé ẹran-ara ati ẹ̀jẹ̀ kò lè jogún ìjọba Ọlọrun, ati pé ohun tíí bàjẹ́ kò lè jogún ohun tí kì í bàjẹ́.
Ara, ohun ti mo n so ni pe eran-ara ati eje ko le jogun ijoba Olorun, ati pe ohun tii baje ko le jogun ohun ti ki i baje.
Ǹjẹ́ bí Ọlọ́run bá wọ koríko igbó ní aṣọ bẹ́ẹ̀, èyí tí ó wà níhìn-ín lónìí ti a sì gbà sínú iná lọ́la, kò ha ṣe ni ṣe yín lọ́ṣọ̀ọ́ tó bẹ́ẹ̀ àti jù bẹ́ẹ̀ lọ, ẹ̀yin tí ìgbàgbọ́ yín kéré
Nje bi Olorun ba wo koriko igbo ni aso bee, eyi ti o wa nihin-in lonii ti a si gba sinu ina lola, ko ha se ni se yin losoo to bee ati ju bee lo, eyin ti igbagbo yin kere
Mátíù , Máàkù àti Lúùkù ròyìn pé láti wákàtí kẹfà , lẹ́yìn tí wọ́n ti gbé Jésù kọ́ sórí òpó igi , òkùnkùn ṣú bo ilẹ̀ náà , “ títí di wákàtí kẹsàn - án . ” — Mát .
Matiu , Maaku ati Luuku royin pe lati wakati kefa , leyin ti won ti gbe Jesu ko sori opo igi , okunkun su bo ile naa , " titi di wakati kesan - an . " -- Mat .
Bíbélì tún jẹ́ ká mọ ohun tí Ọlọ́run ní lọ́kàn fún àwa èèyàn .
Bibeli tun je ka mo ohun ti Olorun ni lokan fun awa eeyan .
Ìfẹ́ fún Ọlọ́run àti ìfẹ́ fún aládùúgbò ẹni ló máa darí rẹ̀ .
Ife fun Olorun ati ife fun aladuugbo eni lo maa dari re .
Èyí tí mo sọ kẹ́lẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ sì etí yín ni kí ẹ kéde rẹ́ lórí òrùlé
Eyi ti mo so kelelekele si eti yin ni ki e kede re lori orule
Òun yóò pa ọ́ ní orí , ìwọ yóò sì pa á ní gìgísẹ̀ . ”
Oun yoo pa o ni ori , iwo yoo si pa a ni gigise . ”
Síbẹ̀ , àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù jẹ́ ká mọ̀ ní 1 Tímótì 2 : 4 , pé ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí ‘ gbogbo onírúurú ènìyàn wá ní ìmọ̀ pípéye nípa òtítọ́ . ’
Sibe , apositeli Poolu je ka mo ni 1 Timoti 2 : 4 , pe ife Olorun ni pe ki ' gbogbo oniruuru eniyan wa ni imo pipeye nipa otito . '
Nígbà náà ó sì tún kọjá Hésórónì lọ sí Ádárì, ó sì tún yípo yíká lọ sí Kákà
Nigba naa o si tun koja Hesoroni lo si Adari, o si tun yipo yika lo si Kaka
Kí nìdí ?
Ki nidi ?
Wọ́n tún kọ́ ọ ní Òfin Ọlọ́run .
Won tun ko o ni Ofin Olorun .
• Orí kí ni ojúlówó ìgbàgbọ́ dá lé , báwo lèyí sì ṣe lè jẹ́ ká ní ìgboyà ?
• Ori ki ni ojulowo igbagbo da le , bawo leyi si se le je ka ni igboya ?
Àkòrí ọ̀rọ̀ rẹ̀ ni , “ Pẹ̀lú Gbogbo Ohun Tẹ́ Ẹ Ti Gbọ́ Yìí , Kí Lẹ Máa Ṣe ” ?
Akori oro re ni , " Pelu Gbogbo Ohun Te E Ti Gbo Yii , Ki Le Maa Se " ?
Nítorí náà, nisinsinyii, ẹ kíyèsí àwọn ohun tí ń ṣẹlẹ̀ si yín:
Nitori naa, nisinsinyii, e kiyesi awon ohun ti n sele si yin:
Ìwé ìròyìn náà ṣàlàyé pé : “ Iṣẹ́ ètò MSB yìí ni láti ṣa ohun tó ju ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n irú ọ̀wọ́ àwọn irúgbìn kan jọ kí wọ́n sì fi wọ́n pa mọ́ — ìyẹn ju ìpín mẹ́wàá nínú ọgọ́rùn - ún àwọn nǹkan ọ̀gbìn tó ń so èso lọ . ”
Iwe iroyin naa salaye pe : “ Ise eto MSB yii ni lati sa ohun to ju egberun meeedogbon iru owo awon irugbin kan jo ki won si fi won pa mo — iyen ju ipin mewaa ninu ogorun - un awon nnkan ogbin to n so eso lo . ”
Ẹ kí Rufọsi, àṣàyàn onigbagbọ ati ìyá rẹ̀ tí ó tún jẹ́ ìyá tèmi náà.
E ki Rufosi, asayan onigbagbo ati iya re ti o tun je iya temi naa.
gésúrì
gesuri
Jésù fi ọwọ́ gidi mú ìtumọ̀ orúkọ tí Ọlọ́run fún un yìí .
Jesu fi owo gidi mu itumo oruko ti Olorun fun un yii .
bamótì
bamoti
Lẹ́sẹ̀ kan náà , ó wá rí pé àwọn tó kù ò tiẹ̀ sún mọ́ òun rárá nínú ṣíṣe gbogbo nǹkan fínnífínní , wọn ò sì já fáfá tó bí òun ṣe fẹ́ .
Lese kan naa , o wa ri pe awon to ku o tie sun mo oun rara ninu sise gbogbo nnkan finnifinni , won o si ja fafa to bi oun se fe .
Wọ́n sábà máa ń fi iyọ̀ àti òróró tàbí àwọn èròjà tí wọ́n mú jáde látara igi ólífì sí i , wọ́n sì máa ń fi ọbẹ̀ tó láwọn èròjà tó ń mú oúnjẹ dùn tàbí ohun mímu eléso sí i lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan . ”
Won saba maa n fi iyo ati ororo tabi awon eroja ti won mu jade latara igi olifi si i , won si maa n fi obe to lawon eroja to n mu ounje dun tabi ohun mimu eleso si i leekookan . "
àgbára
agbara
Kinniun alágbára a máa kú,nítorí àìrí ẹran pa jẹ,àwọn ọmọ abo kinniun a sì fọ́nká.
Kinniun alagbara a maa ku,nitori airi eran pa je,awon omo abo kinniun a si fonka.
1 : 18 - 25 ; Lúùkù 1 : 26 - 35 .
1 : 18 - 25 ; Luuku 1 : 26 - 35 .
Àwa méjèèjì la fẹ́ máa bá iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún nìṣó , ìdí nìyẹn tí inú wa fi dùn gan - an nígbà tí wọ́n yàn mí sí iṣẹ́ alábòójútó àyíká lẹ́yìn tí mo kúrò ní Bẹ́tẹ́lì .
Awa mejeeji la fe maa ba ise isin alakooko kikun niso , idi niyen ti inu wa fi dun gan - an nigba ti won yan mi si ise alaboojuto ayika leyin ti mo kuro ni Beteli .
Báwo ló ṣe yẹ ká máa lo àǹfààní iṣẹ́ ìsìn tá a ní nínú ètò Jèhófà ?
Bawo lo se ye ka maa lo anfaani ise isin ta a ni ninu eto Jehofa ?
Tí mo bá ń mu sìgá tàbí àwọn nǹkan tí wọ́n fi tábà ṣe ǹjẹ́ ó tiẹ̀ kan Ọlọ́run ?
Ti mo ba n mu siga tabi awon nnkan ti won fi taba se nje o tie kan Olorun ?
Yàtọ̀ síyẹn , ìdá mẹ́rin àwọn tó ń gbé láyé ni kò rílé gidi gbé , ìdá márùn - ún ni kò jàǹfààní ètò ìlera tó bójú mu .
Yato siyen , ida merin awon to n gbe laye ni ko rile gidi gbe , ida marun - un ni ko janfaani eto ilera to boju mu .
Kíkópa déédéé nínú iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere náà ń ràn wá lọ́wọ́ láti gbájú mọ́ nǹkan tẹ̀mí .
Kikopa deedee ninu ise iwaasu ihin rere naa n ran wa lowo lati gbaju mo nnkan temi .
Ìjọsìn Tòótọ́ So Ìdílé Kan Pọ̀ , 8 / 15
Ijosin Tooto So Idile Kan Po , 8 / 15
Bẹ́ẹ̀ ni o !
Bee ni o !
Ìkejì , a gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ máa darí wa .
Ikeji , a gbodo je ki emi mimo re maa dari wa .
A lè rí irú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí lára àwọn ògiri ilé àtàwọn ibòmíràn nígboro ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀ - èdè kárí ayé .
A le ri iru oro wonyi lara awon ogiri ile atawon ibomiran nigboro ni opo orile - ede kari aye .
sìdónì
sidoni
Ó yẹ ká máa bọlá fáwọn ọkùnrin wọ̀nyí , ká sì máa tì wọ́n lẹ́yìn gbágbáágbá , yálà wọ́n jẹ́ ara ẹni àmì òróró tàbí wọn kì í ṣe ara wọn .
O ye ka maa bola fawon okunrin wonyi , ka si maa ti won leyin gbagbaagba , yala won je ara eni ami ororo tabi won ki i se ara won .
Ilé Ìwé Jẹ́lé - Ó - Sinmi Tí Kò Ní Ohun Ìṣeré Ọmọdé , 10 / 8
Ile Iwe Jele - O - Sinmi Ti Ko Ni Ohun Isere Omode , 10 / 8
Kí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá sọ ?
Ki ni awon omo Isireli wa so ?
Kí ni fìlà yó ṣe lórí ògógó? Ata ni yó ṣi.
Ki ni fila yo se lori ogogo? Ata ni yo si.
Nígbà tó yá àwọn méjèèjì bẹ̀rẹ̀ sí fi ohun tí wọ́n kọ́ ṣèwà hù .
Nigba to ya awon mejeeji bere si fi ohun ti won ko sewa hu .
Ó Fúnni Nírètí
O Funni Nireti
Oore l'Elédùwà nr ṣe fọmọ adáríhunrun
Oore l'Eleduwa nr se fomo adarihunrun
Torí náà , ńṣe ni onítọ̀hún ń lo okun rẹ̀ dà nù !
Tori naa , nse ni onitohun n lo okun re da nu !
Ọ̀rọ̀ kàbìtì mà nìyẹn jẹ́ nípa bí àkókò wa ṣe máa kún fún ìbẹ̀rù tó o !
Oro kabiti ma niyen je nipa bi akoko wa se maa kun fun iberu to o !
Ilé iṣẹ́ rédíò tó lé ní irínwó [ 400 ] ló máa ń bá wa gbé àwọn àsọyé tá a sọ ní àwọn àpéjọ wa sáfẹ́fẹ́ .
Ile ise redio to le ni irinwo [ 400 ] lo maa n ba wa gbe awon asoye ta a so ni awon apejo wa safefe .
ẹni tí ó di alufaa nípa agbára ìyà tí kò lópin, tí kì í ṣe nípa ìlànà àṣẹ tí a ti ọwọ́ eniyan ṣe ètò.
eni ti o di alufaa nipa agbara iya ti ko lopin, ti ki i se nipa ilana ase ti a ti owo eniyan se eto.
mú kí iṣẹ́ rẹ̀ wuyì
mu ki ise re wuyi
Síbẹ̀ náà , mi ò ní padà sílé , nítorí mo mọ̀ pé iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa yóò jẹ́ kí àwa àti ẹnikẹ́ni tó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ wa ní ìgbàlà .
Sibe naa , mi o ni pada sile , nitori mo mo pe ise ojise wa yoo je ki awa ati enikeni to ba gbo oro wa ni igbala .
A kíyè sí i pé àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù pe ìjọba táwọn èèyàn gbé kalẹ̀ ní “ ìránṣẹ́ Ọlọ́run sí gbogbo ènìyàn . ”
A kiye si i pe apositeli Poolu pe ijoba tawon eeyan gbe kale ni " iranse Olorun si gbogbo eniyan . "
Òbúkọ onírun náà ni ọba Giriki, ìwo ńlá ti ó wà láàrín ojú u rẹ̀ ni ọba àkọ́kọ́.
Obuko onirun naa ni oba Giriki, iwo nla ti o wa laarin oju u re ni oba akoko.
Bí nǹkan sì ṣe máa ń rí lára àwa èèyàn máa ń yàtọ̀ síra nígbà míì , a lè nífẹ̀ẹ́ , a lè kórìíra , a sì lè bínú .
Bi nnkan si se maa n ri lara awa eeyan maa n yato sira nigba mii , a le nifee , a le koriira , a si le binu .
• Kí ló lè ran Kristẹni kan lọ́wọ́ láti pinnu bóyá eré ìtura kan ṣàǹfààní ?
• Ki lo le ran Kristeni kan lowo lati pinnu boya ere itura kan sanfaani ?
óye
oye
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | ǸJẸ́ ỌLỌ́RUN BÌKÍTÀ NÍPA RẸ ?
KOKO IWAJU IWE | NJE OLORUN BIKITA NIPA RE ?
Wéwèé ṣáájú !
Wewee saaju !
Kí Ló Mú Kí Wọ́n Di Nọ́ọ̀sì ?
Ki Lo Mu Ki Won Di Noosi ?
Ààyá bọ́ sílẹ̀, ó bọ́ sílé.
Aaya bo sile, o bo sile.
Àwọn Ẹlẹ́rìí márùndínlógójì gbéra láti lọ wàásù ní àgbègbè tí a kò pín fúnni ní Tineg , lágbègbè Abra , níbi tí wọn ò tíì bẹ̀ wò fún ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n .
Awon Elerii marundinlogoji gbera lati lo waasu ni agbegbe ti a ko pin funni ni Tineg , lagbegbe Abra , nibi ti won o tii be wo fun odun metadinlogbon .
3 Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Máa Bọ̀wọ̀ Fúnni
3 Ko Awon Omo Re Lati Maa Bowo Funni
Ọ̀pọ̀ àwọn ará tó wàásù fáwọn èèyàn wọn tó dà bíi pé wọn ò lè di Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló ti rí i pé ó yọrí sí rere .
Opo awon ara to waasu fawon eeyan won to da bii pe won o le di Elerii Jehofa lo ti ri i pe o yori si rere .
nínú ibojì wọn bí ìgbà tíwọn n
ninu iboji won bi igba tiwon n
Èrò mi lórí ọ̀rọ̀ yìí ni pé ohun tí ó dára jùlọ fun yín ni. Nígbà tí kì í tíí ṣe pé ẹ ti ń ṣe é nìkan ni, ṣugbọn tìfẹ́tìfẹ́ ni ẹ ti fi ń ṣe é láti ọdún tí ó kọjá,
Ero mi lori oro yii ni pe ohun ti o dara julo fun yin ni. Nigba ti ki i tii se pe e ti n se e nikan ni, sugbon tifetife ni e ti fi n se e lati odun ti o koja,
Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ronú pé bí àkókò ti ń lọ á ṣeé ṣe fáwọn láti wo àwọn àrùn tó jẹ́ àjogúnbá nípa fífa àwọn àbùdá tó lè wo àrùn náà sàn sára aláìsàn .
Awon onimo sayensi ronu pe bi akoko ti n lo a see se fawon lati wo awon arun to je ajogunba nipa fifa awon abuda to le wo arun naa san sara alaisan .
Ìmọ̀ yẹn , pa pọ̀ pẹ̀lú ìgbàgbọ́ tí wọ́n ní nínú ohun tí wọ́n gbọ́ lẹ́nu Pétérù , ló jẹ́ kó ṣeé ṣe láti batisí wọn “ ní orúkọ Baba àti ti Ọmọ àti ti ẹ̀mí mímọ́ . ”
Imo yen , pa po pelu igbagbo ti won ni ninu ohun ti won gbo lenu Peteru , lo je ko see se lati batisi won " ni oruko Baba ati ti Omo ati ti emi mimo . "
Nígbà tí orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì kọ̀ láti ní ìgbàgbọ́ nínú Jésù tí wọ́n sì pa á , Jèhófà ò jẹ́ kí wọ́n jẹ́ orúkọ mọ́ òun mọ́ .
Nigba ti orile - ede Isireli ko lati ni igbagbo ninu Jesu ti won si pa a , Jehofa o je ki won je oruko mo oun mo .
Ọkùnrin kì í ké, akọ igi kì í ṣoje.
Okunrin ki i ke, ako igi ki i soje.
Sáàmù 29
Saamu 29
Kí ló wá ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn náà ?
Ki lo wa sele leyin naa ?
150. Nítorí náà bẹòẹ̀ẹ̀rẹ̀ lỌWwỌ Wọn
150. Nitori naa beoeere lOWwO Won
Ọ̀gbẹ́ni Tischendorf rèé
Ogbeni Tischendorf ree
Kàkà bẹ́ẹ̀ , ohun tó túmọ̀ sí ni pé àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà tó wà lórí ilẹ̀ ayé máa fi tọkàntọkàn kópa nínú ayẹyẹ ìṣẹ́gun tó máa wáyé lẹ́yìn tí ayé Sátánì bá ti pa run . — Sáàmù 145 : 20 ; Ìṣípayá 20 : 1 - 3 .
Kaka bee , ohun to tumo si ni pe awon iranse Jehofa to wa lori ile aye maa fi tokantokan kopa ninu ayeye isegun to maa waye leyin ti aye Satani ba ti pa run . -- Saamu 145 : 20 ; Isipaya 20 : 1 - 3 .
Àmọ́ , ìyàwó mi to yàrá náà dáadáa , ó sì bójú mu .
Amo , iyawo mi to yara naa daadaa , o si boju mu .
Ọ̀jọ̀gbọ́n Xolela Mangcu , ọmọ ilẹ̀ Áfíríkà kan tó ń ṣàyẹ̀wò ọ̀rọ̀ ìṣèlú , sọ pé : “ Tá a bá wo ìtàn ayé , a óò rí i pé àìmọye ìgbà ni ọ̀rọ̀ dída ẹ̀sìn pọ̀ mọ́ ìṣèlú ti fa ogun táwọn èèyàn ti fẹ̀mí ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn ṣòfò . ”
Ojogbon Xolela Mangcu , omo ile Afirika kan to n sayewo oro iselu , so pe : “ Ta a ba wo itan aye , a oo ri i pe aimoye igba ni oro dida esin po mo iselu ti fa ogun tawon eeyan ti femi opo repete eeyan sofo . ”
Ó ní : “ Ẹ gbé ojú yín sókè réré , kí ẹ sì wò .
O ni : " E gbe oju yin soke rere , ki e si wo .
Doegi, olórí darandaran Saulu, ará Edomu wà níbẹ̀ ní ọjọ́ náà, nítorí pé ó ń jọ́sìn níwájú OLUWA.
Doegi, olori darandaran Saulu, ara Edomu wa nibe ni ojo naa, nitori pe o n josin niwaju OLUWA.
Nígbà náà ni wọn kígbe ní ohùn rara, wọn sí di etí wọ́n, gbogbo wọn sì sáré sí i, wọ́n sì rọ́ lù ú, wọ́n sì wọ́ ọ sẹ́yìn òde ìlú, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ ọ́ ní òkúta
Nigba naa ni won kigbe ni ohun rara, won si di eti won, gbogbo won si sare si i, won si ro lu u, won si wo o seyin ode ilu, won si bere si so o ni okuta
Níwọ̀n bí ìgbéyàwó ọmọkùnrin ẹni , ọmọbìnrin ẹni , arákùnrin tàbí arábìnrin ẹni ti sábà máa ń túmọ̀ sí pé ẹni náà ń lọ dá agbo ilé tiẹ̀ sílẹ̀ , èyí sábà máa ń mú kí ìdílé ní oríṣiríṣi èrò .
Niwon bi igbeyawo omokunrin eni , omobinrin eni , arakunrin tabi arabinrin eni ti saba maa n tumo si pe eni naa n lo da agbo ile tie sile , eyi saba maa n mu ki idile ni orisirisi ero .
Àmọ́ , tó bá jẹ́ pé ìbéèrè tó o béèrè ni àwọn èèyàn fi rántí rẹ ńkọ́ ?
Amo , to ba je pe ibeere to o beere ni awon eeyan fi ranti re nko ?
Ǹjẹ́ O Lè Ṣàlàyé ?
Nje O Le Salaye ?
Bíbélì kò sọ fún wa .
Bibeli ko so fun wa .
Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe fún aráyé ?
Ki ni Ijoba Olorun maa se fun araye ?
Èyí jẹ́ ká rí i pé táwọn èèyàn bá máa gbádùn òmìnira tí wọ́n ní , ó pọn dandan káwọn òfin kan wà tí wọ́n á máa tẹ̀ lé .
Eyi je ka ri i pe tawon eeyan ba maa gbadun ominira ti won ni , o pon dandan kawon ofin kan wa ti won a maa te le .
* — Ẹ́sítérì 4 : 9 - 11 .
* — Esiteri 4 : 9 - 11 .
Nínú ọ̀rọ̀ wọn , Jeff rí i pé bó tilẹ̀ jẹ́ pé tọkọtaya náà ti lo ọdún méjìlá ní Amẹ́ríkà , wọ́n ò tíì rí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà rí , bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ò tíì bá wọn sọ̀rọ̀ rí !
Ninu oro won , Jeff ri i pe bo tile je pe tokotaya naa ti lo odun mejila ni Amerika , won o tii ri awon Elerii Jehofa ri , bee ni won o tii ba won soro ri !
Kí ló gba pé kéèyàn ṣe ? Ǹjẹ́ ẹnì kan ti sọ fún ẹ rí pé òun gba ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n gbọ́ torí pé ẹ̀rí wà nínú sáyẹ́ǹsì pé òótọ́ ni , ṣùgbọ́n kò sí ẹ̀rí kankan tó fi hàn pé Ọlọ́run wà , àfi kéèyàn ṣáà ti gbà á gbọ́ ?
Ki lo gba pe keeyan se ? Nje eni kan ti so fun e ri pe oun gba eko efoluson gbo tori pe eri wa ninu sayensi pe ooto ni , sugbon ko si eri kankan to fi han pe Olorun wa , afi keeyan saa ti gba a gbo ?
Báwo ni àwọn Júù ìgbàanì ṣe nírìírí “ ọ̀run tuntun àti ilẹ̀ ayé tuntun ” ?
Bawo ni awon Juu igbaani se niriiri “ orun tuntun ati ile aye tuntun ” ?
( Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́ )
( Wo abe EKO BIBELI > AWON ODO )
Pẹ̀lú ìtìlẹyìn owó látọ̀dọ̀ Hendrik Niclaes tó jẹ́ aṣáájú ẹ̀ya ìsìn Ánábatíìsì kan báyìí , Plantin bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìwé títẹ̀ .
Pelu itileyin owo latodo Hendrik Niclaes to je asaaju eya isin Anabatiisi kan bayii , Plantin bere ise iwe tite .
Ó mú wa lọ sínú ilé rẹ̀ , ó sì sọ fún wa pé , ojoojúmọ́ lòun máa ń gbàdúrà sí Jèhófà pé kó rán àwọn Ẹlẹ́rìí rẹ̀ láti wá kọ́ ìdílé òun àtàwọn tí àwọn jọ ń sọ èdè O’dam lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .
O mu wa lo sinu ile re , o si so fun wa pe , ojoojumo loun maa n gbadura si Jehofa pe ko ran awon Elerii re lati wa ko idile oun atawon ti awon jo n so ede O’dam lekoo Bibeli .
Nígbà náà ni ọba àti gbogbo Israẹli rú ẹbọ níwájú .
Nigba naa ni oba ati gbogbo Israeli ru ebo niwaju .
Nígbà tí ọ̀pọ̀ eniyan péjọ yí i ká, ó bẹ̀rẹ̀ sí wí pé, “Ìran burúkú ni ìran yìí; ó ń wá àmì. Kò sí àmì kan tí a óo fún un àfi àmì Jona.
Nigba ti opo eniyan pejo yi i ka, o bere si wi pe, "Iran buruku ni iran yii; o n wa ami. Ko si ami kan ti a oo fun un afi ami Jona.
Ìyẹn jẹ́ kó ṣeé ṣe fún mi láti jẹ́rìí fún un , mo sì gba ibi wàhálà yẹn kọjá láìfarapa .
Iyen je ko see se fun mi lati jerii fun un , mo si gba ibi wahala yen koja laifarapa .
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 4 , 5 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 4 , 5 ]
Kódà Òwe 21 : 1 sọ fún wa pé : “ Ọkàn - àyà ọba dà bí ìṣàn omi ní ọwọ́ Jèhófà .
Koda Owe 21 : 1 so fun wa pe : “ Okan - aya oba da bi isan omi ni owo Jehofa .
Fún ìsọfúnni síwájú sí i , wo àpilẹ̀kọ náà “ Ǹjẹ́ O Lè ‘ Ré Kọjá Lọ Sí Makedóníà ’ ? ”
Fun isofunni siwaju si i , wo apileko naa “ Nje O Le ‘ Re Koja Lo Si Makedonia ’ ? ”
Káyọ̀dé : Ṣé ẹ rí i , mo sọ fún ẹnì kan tá a jọ ń ṣiṣẹ́ nípa bí mo ṣe gbádùn ìwé tí ẹ fún mi lọ́jọ́ sí .
Kayode : Se e ri i , mo so fun eni kan ta a jo n sise nipa bi mo se gbadun iwe ti e fun mi lojo si .
Síbẹ̀ , ó ti fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ẹgbàá [ 2,000 ] ọdún sẹ́yìn tí àsọtẹ́lẹ̀ yìí ti wà lákọọ́lẹ̀ nínú Bíbélì !
Sibe , o ti feree to egbaa [ 2,000 ] odun seyin ti asotele yii ti wa lakoole ninu Bibeli !
Nígbà míì , mo máa ń rò ó pé ó kúkú sàn kí n pa wọ́n , kí èmi náà sì pa ara mi .
Nigba mii , mo maa n ro o pe o kuku san ki n pa won , ki emi naa si pa ara mi .
250 ° sí 350 ° C .
250 ° si 350 ° C .
Nítorí bí Ọlọ́run kò bá dá ẹ̀ka-ìyẹ́ka sí, kíyèsára kí ó má ṣe ṣe àìdá ìwọ náà sí.
Nitori bi Olorun ko ba da eka-iyeka si, kiyesara ki o ma se se aida iwo naa si.