diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Àwọn Kristẹni ọkùnrin tó fẹ́ máa sin àwọn olùjọsìn ẹlẹgbẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí alàgbà àti ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ náà ní ète rere lọ́kàn .
Awon Kristeni okunrin to fe maa sin awon olujosin elegbe won gege bi alagba ati iranse ise ojise naa ni ete rere lokan .
mo bẹ̀rù pé àwọn ará Lámánì yíò pa àwọn ènìyàn yĩ run; nítorítí wọn kò ronúpìwàdà, Sátánì sì nrú wọn sókè títí ní ìbínú sí ara wọn.
mo beru pe awon ara Lamani yio pa awon eniyan yi run; nitoriti won ko ronupiwada, Satani si nru won soke titi ni ibinu si ara won.
somọ́lẹ̀
somole
Ibi odi yẹn , láti Odò Volkhov
Ibi odi yen , lati Odo Volkhov
Nígbà tí Jèhófà tún ń sọ nípa ọ̀nà tí wọ́n máa gbà kọ́ àgọ́ ìjọsìn náà , ó ní : “ Ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí èmi yóò fi hàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí àwòṣe àgọ́ ìjọsìn àti àwòṣe gbogbo ohun èlò inú rẹ̀ , bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ ṣe é . ”
Nigba ti Jehofa tun n so nipa ona ti won maa gba ko ago ijosin naa , o ni : " Ni ibamu pelu gbogbo ohun ti emi yoo fi han o gege bi awose ago ijosin ati awose gbogbo ohun elo inu re , bee ni ki e se e . "
bẹ̀rù Olúwa nbá ara wọn sọ̀rọ̀ nígbàkũgbà, Olúwa sì fetísílẹ̀, ó sì gbọ́; a sì kọ ìwé-ìrántí kan níwájú rẹ̀ fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa, tí wọ́n sì nrántí, tí wọ́n sì bẹ̀rù orúkọ rẹ̀.
beru Oluwa nba ara won soro nigbakugba, Oluwa si fetisile, o si gbo; a si ko iwe-iranti kan niwaju re fun awon ti o beru Oluwa, ti won si nranti, ti won si beru oruko re.
kádésí
kadesi
Ó fẹ́ kí á mọ̀ nípa òun .
O fe ki a mo nipa oun .
séráíà
seraia
Ephraim tẹ̀ síwájú kíákíá .
Ephraim te siwaju kiakia .
Ṣùgbọ́n , “ dírágónì ńlá aláwọ̀ iná ” jẹ́ ọ̀nà tó ṣe wẹ́kú láti gbà ṣàpèjúwe ẹ̀mí apanijẹ , adáyàjáni , alágbára , àti apanirun tí Sátánì ní .
Sugbon , " diragoni nla alawo ina " je ona to se weku lati gba sapejuwe emi apanije , adayajani , alagbara , ati apanirun ti Satani ni .
Lónìí , ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé níbi gbogbo ni ọ̀pọ̀ àwọn tó mọṣẹ́ ìṣègùn òyìnbó dunjú ti mọ agbára ìwòsàn tí àwọn ewé kan ní .
Lonii , o feree je pe nibi gbogbo ni opo awon to mose isegun oyinbo dunju ti mo agbara iwosan ti awon ewe kan ni .
Bákan náà , má máa fara ẹ wé àwọn ẹlòmíì láìrí bí nǹkan ṣe rí dáadáa .
Bakan naa , ma maa fara e we awon elomii lairi bi nnkan se ri daadaa .
Nínú ọ̀rọ̀ wọn ní FIFA, àwọn akọbúlọ́ọ̀gù náà sọ wípé ìkẹ́gbẹ́ẹ wọn nínú Ohùn Àgbáyé ṣe gudugudu méje yàyà mẹ́fà ní àsìkò tí àwọn ń fi aṣọ pénpé ro oko ọba. Ní ètò ìtàkùrọ̀sọ wọn, wọ́n gbé orí yìn fún ìpolongo Ohùn Àgbáyé tí ó ṣe iṣẹ́ ribiribi tí ó mú àwọn wà láyé.
Ninu oro won ni FIFA, awon akobuloogu naa so wipe ikegbee won ninu Ohun Agbaye se gudugudu meje yaya mefa ni asiko ti awon n fi aso penpe ro oko oba. Ni eto itakuroso won, won gbe ori yin fun ipolongo Ohun Agbaye ti o se ise ribiribi ti o mu awon wa laye.
Báwo ?
Bawo ?
Wọn ò lè pèsè ààbò tó máa wà pẹ́ títí .
Won o le pese aabo to maa wa pe titi .
( Ka Sáàmù 25 : 14 . )
( Ka Saamu 25 : 14 . )
Kò sọ pé kí ọkùnrin náà ṣáá ní ìgbàgbọ́ kódà bí kò bá rí èrè kankan gbà .
Ko so pe ki okunrin naa saa ni igbagbo koda bi ko ba ri ere kankan gba .
[ Àwọn àwòrán tó wà ní ojú ìwé 8 , 9 ]
[ Awon aworan to wa ni oju iwe 8 , 9 ]
Ńṣe làwọn tó bá fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ Jésù máa ń tẹ́tí bẹ̀lẹ̀jẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ̀ .
Nse lawon to ba fe kekoo lodo Jesu maa n teti beleje si oro re .
kasluhimu
kasluhimu
Ó tọ́ka sáwọn iṣẹ́ rere tó ṣe láti fi hàn pé Ọlọ́run ń ti òun lẹ́yìn .
O toka sawon ise rere to se lati fi han pe Olorun n ti oun leyin .
Nítorí náà , ìdààmú tàbí àníyàn lè bá ẹni náà .
Nitori naa , idaamu tabi aniyan le ba eni naa .
Tá a bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ Ọlọ́run , a gbọ́dọ̀ “ jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ ní èrò inú . ”
Ta a ba fe je ore Olorun , a gbodo “ je onirele ni ero inu . ”
Kódà , mo tún ń bá àwọn tó ń gba owó èlé gọbọi lórí owó tí wọ́n ń yá àwọn èèyàn sin owó , torí pé mi ò kì í bẹ̀rù ẹnikẹ́ni .
Koda , mo tun n ba awon to n gba owo ele goboi lori owo ti won n ya awon eeyan sin owo , tori pe mi o ki i beru enikeni .
* Ọjà ẹrú ni wọ́n ti ta ọ̀pọ̀ lára wọn .
* Oja eru ni won ti ta opo lara won .
Mélòó la fẹ́ kà lára àwọn tó ti rí ikú àìtọ́jọ́ he , bí wọ́n ti ń ṣe ohun tí wọ́n gbà gbọ́ pé ó tọ̀nà ?
Meloo la fe ka lara awon to ti ri iku aitojo he , bi won ti n se ohun ti won gba gbo pe o tona ?
tí ó taari wọn ṣubú ní ìbínú rẹ̀ Tí ó mi ilẹ̀ ayé tìtì kúrò ní ipò rẹ̀, ọwọ̀n rẹ̀ sì mì tìtì Ó pàṣẹ fún oòrùn kò sì le è ràn kí ó sì dí ìmọ́lẹ̀ ìràwọ̀ mọ́
ti o taari won subu ni ibinu re Ti o mi ile aye titi kuro ni ipo re, owon re si mi titi O pase fun oorun ko si le e ran ki o si di imole irawo mo
Kódà , ọ̀gá àgbà náà fi kún un pé , “ gbogbo ohun tá à ń rí láyìíká fi hàn pé ńṣe ni bí àyíká wa ṣe rí lónìí wá ń burú sí i ju bó ṣe rí nígbà Àpérò Ìparapọ̀ Orílẹ̀ - Èdè tó wáyé lọ́dún 1992 . ”
Koda , oga agba naa fi kun un pe , “ gbogbo ohun ta a n ri layiika fi han pe nse ni bi ayika wa se ri lonii wa n buru si i ju bo se ri nigba Apero Iparapo Orile - Ede to waye lodun 1992 . ”
Jésù wí fún un pé, Arákùnrin rẹ yóò jíǹde
Jesu wi fun un pe, Arakunrin re yoo jinde
Àwọn tí ń sùn sórí ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe gbé! Àwọn tí wọ́n nà kalẹ̀ lórí ìrọ̀gbọ̀kú wọn, tí wọn ń jẹ ẹran ọ̀dọ́ aguntan, ati ti ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù láti inú agbo ẹran wọn!
Awon ti n sun sori ibusun ti won fi eyin erin se gbe! Awon ti won na kale lori irogboku won, ti won n je eran odo aguntan, ati ti egboro maaluu lati inu agbo eran won!
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
Awon Onkawe Wa Beere Pe . . .
Àwọn màlúù àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ó ń tú ilẹ̀ yóò jẹ oúnjẹ àdídùn tí a fi amúga àti ṣọ́bìrì fọ́nkálẹ̀
Awon maluu ati awon ketekete ti o n tu ile yoo je ounje adidun ti a fi amuga ati sobiri fonkale
‘Ẹ fi Merosi bú’ ni angẹli wí.‘Ẹ fi àwọn ènìyàn inú rẹ̀ bú ìbú kíkorò,nítorí wọn kò wá sí ìrànlọ́wọ́ ,láti dojúkọ àwọn alágbára.’
‘E fi Merosi bu’ ni angeli wi.‘E fi awon eniyan inu re bu ibu kikoro,nitori won ko wa si iranlowo ,lati dojuko awon alagbara.’
Ákúílà àti Pírísílà tún ran Ápólò lọ́wọ́ , ìyẹn Kristẹni tó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ nì , ẹni tó ń kọ́ àwọn olùgbé Éfésù nípa Jésù Kristi .
Akuila ati Pirisila tun ran Apolo lowo , iyen Kristeni to je sorosoro ni , eni to n ko awon olugbe Efesu nipa Jesu Kristi .
Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run .
Bibeli je ka mo pe Jehofa ni oruko Olorun .
ibòòji
ibooji
Ẹrú ni ọ́ nígbà tí a fi pè ọ́? Má ṣe gbé e lékàn. Ṣugbọn bí o bá ní anfaani láti di òmìnira, lo anfaani rẹ.
Eru ni o nigba ti a fi pe o? Ma se gbe e lekan. Sugbon bi o ba ni anfaani lati di ominira, lo anfaani re.
Ìran àwọn wòlíì rẹjẹ́ kìkì ẹ̀tàn láìní ìwọ̀n;wọn kò sì fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ hàntí yóò mú ìgbèkùn kúrò fún ọ.Àwọn òrìṣà tí wọ́n fún ọjẹ́ èké àti ìmúniṣìnà.
Iran awon wolii reje kiki etan laini iwon;won ko si fi ese re hanti yoo mu igbekun kuro fun o.Awon orisa ti won fun oje eke ati imunisina.
Iṣẹ́ mi ojoojúmọ́ ni kí n mú kí ahéré táa ń gbé wà ní mímọ́ tónítóní , kí n hunṣọ , kí n sì tọ́jú àwọn àgùntàn wa .
Ise mi ojoojumo ni ki n mu ki ahere taa n gbe wa ni mimo tonitoni , ki n hunso , ki n si toju awon aguntan wa .
Ó sọ fún gómìnà ará Róòmù nì , Pọ́ńtíù Pílátù , pé : “ Nítorí èyí ni a ṣe bí mi , nítorí èyí sì ni mo ṣe wá sí ayé , kí n lè jẹ́rìí sí òtítọ́ . ”
O so fun gomina ara Roomu ni , Pontiu Pilatu , pe : " Nitori eyi ni a se bi mi , nitori eyi si ni mo se wa si aye , ki n le jerii si otito . "
Wọ́n rú àwọn eniyan ati àwọn àgbààgbà ati àwọn amòfin nídìí, ni wọ́n bá mú un, wọ́n fà á lọ siwaju àwọn ìgbìmọ̀.
Won ru awon eniyan ati awon agbaagba ati awon amofin nidii, ni won ba mu un, won fa a lo siwaju awon igbimo.
Káínì wí fún Ábélì arákùnrin rẹ̀ pé, Jẹ́ kí a lọ sí oko
Kaini wi fun Abeli arakunrin re pe, Je ki a lo si oko
àti àwọn tí ô n gba ààwẹ̀ lọkùnrin
ati awon ti o n gba aawe lokunrin
Ọba Madoni ọ̀kanọba Hasori ọ̀kan
Oba Madoni okanoba Hasori okan
Kúòdà bí mo bá mú ìtọsọnà tô dára
Kuoda bi mo ba mu itosona to dara
Ohun tí àpọ́sítélì yìí ń sọ nínú ẹsẹ yẹn ni pé káwọn Kristẹni máa yẹ ara wọn wò látòkèdélẹ̀ kí wọ́n lè mọ̀ bóyá wọ́n ní kùdìẹ̀ - kudiẹ èyíkéyìí nípa tẹ̀mí , kí wọ́n sì ṣe àtúnṣe tó bá yẹ .
Ohun ti apositeli yii n so ninu ese yen ni pe kawon Kristeni maa ye ara won wo latokedele ki won le mo boya won ni kudie - kudie eyikeyii nipa temi , ki won si se atunse to ba ye .
Torí náà , ẹ jẹ́ ká ṣe gbogbo ohun tá a bá lè ṣe láti ra àkókò pa dà ká lè máa fi ìṣòtítọ́ sin Ọlọ́run “ ìgbà àti àsìkò . ”
Tori naa , e je ka se gbogbo ohun ta a ba le se lati ra akoko pa da ka le maa fi isotito sin Olorun “ igba ati asiko . ”
Hémánì olùkọrin, ọmọ Jóẹ́lì, ọmọ Ṣámúẹ́lì, Ọmọ Élíkánáhì ọmọ Jéróhámù, ọmọ Élíéli, ọmọ Tóhà Ọmọ Ṣúfì, ọmọ Élíkáná, ọmọ Máhátì, ọmọ Ámásáyì, Ọmọ Élíkánà, ọmọ Jóẹ́lì, ọmọ Ásárááhì, ọmọ Ṣéfáníáhì Ọmọ Táhátì, ọmọ Áṣírì, ọmọ Ébíásáfì ọmọ Kóráhì, ọmọ Íṣíhárì, ọmọ Kóhátì ọmọ Léfì, ọmọ Ísírẹ́lì
Hemani olukorin, omo Joeli, omo Samueli, Omo Elikanahi omo Jerohamu, omo Elieli, omo Toha Omo Sufi, omo Elikana, omo Mahati, omo Amasayi, Omo Elikana, omo Joeli, omo Asaraahi, omo Sefaniahi Omo Tahati, omo Asiri, omo Ebiasafi omo Korahi, omo Isihari, omo Kohati omo Lefi, omo Isireli
Bó bá rí bẹ́ẹ̀ , àpẹẹrẹ Hánà lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ .
Bo ba ri bee , apeere Hana le ran e lowo .
Ó yá ẹ wá ṣàlàyé fún mi pé ọ̀rọ̀ ò rí bẹ́ẹ̀ . ”
O ya e wa salaye fun mi pe oro o ri bee . ”
Ẹ̀yin tó kù , ẹ jọ̀ọ́ , mo bẹ̀ yín pé kí ẹ jẹ́ kí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa kọ́ yín lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì , kí ẹ sì máa lọ sí ìpàdé ìjọ wọn .
Eyin to ku , e joo , mo be yin pe ki e je ki awon Elerii Jehofa maa ko yin lekoo Bibeli , ki e si maa lo si ipade ijo won .
Ọ̀nà kejì , wọ́n máa ń kẹ́kọ̀ọ́ látọ̀dọ̀ àwọn míì tó bẹ̀rù Ọlọ́run , ọ̀nà kẹta sì ni bí wọ́n ṣe ń rí ìbùkún Ọlọ́run torí pé wọ́n ń pa àwọn òfin rẹ̀ mọ́ , wọ́n sì ń fi àwọn ìlànà rẹ̀ sílò .
Ona keji , won maa n kekoo latodo awon mii to beru Olorun , ona keta si ni bi won se n ri ibukun Olorun tori pe won n pa awon ofin re mo , won si n fi awon ilana re silo .
irántí
iranti
Jèhófà gan - an làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń kùn sí !
Jehofa gan - an lawon omo Isireli n kun si !
Wàá bọ́ lọ́wọ́ ọ̀pọ̀ ìbànújẹ́ tó o bá dúró dìgbà tó o dàgbà tó , tó o lóye tó , tí òtítọ́ sì jinlẹ̀ dáadáa nínú rẹ kó o tó bẹ̀rẹ̀ sí í fẹ́ ẹnì kan nínú ìjọ Kristẹni .
Waa bo lowo opo ibanuje to o ba duro digba to o dagba to , to o loye to , ti otito si jinle daadaa ninu re ko o to bere si i fe eni kan ninu ijo Kristeni .
( Ka Sáàmù 119 : 9 . )
( Ka Saamu 119 : 9 . )
Jésù mọ̀ pé ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé ìwà àwọn èèyàn ibi tí wọ́n dàgbà sí ló nípa lórí wọn .
Jesu mo pe o see se ko je pe iwa awon eeyan ibi ti won dagba si lo nipa lori won .
ìjà kọ Ọ (Sọlihu) àti àwọn ara ilé
ija ko O (Solihu) ati awon ara ile
▪ Ó fara han □ Máàkù 16 : 1 - 8
▪ O fara han □ Maaku 16 : 1 - 8
Bí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn bá ṣèbẹ̀wò sí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Ìjọ tá a wà ńkọ́ ?
Bi alaboojuto ise isin ba sebewo si Ikekoo Iwe Ijo ta a wa nko ?
ógá
oga
gàgàrà
gagara
Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ táa bá tàpá sí irú ìtọ́ni bẹ́ẹ̀ ?
Ki lo maa n sele taa ba tapa si iru itoni bee ?
13. Àti pé Òun yòò san ẹ̀san
13. Ati pe Oun yoo san esan
Àti nísisìyí ẹ kíyèsĩ, bí
Ati nisisiyi e kiyesi, bi
Ó ní òun á sọ fún wọn pé ìyá wa ti dà wá sílẹ̀ .
O ni oun a so fun won pe iya wa ti da wa sile .
Ní ti àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró tí Pọ́ọ̀lù kọ́kọ́ kọ̀wé sí , jíjẹ́ ‘ ẹrú nínú Olúwa ’ kan fífi àmì òróró yàn wọ́n gẹ́gẹ́ bí ọmọ Ọlọ́run àti arákùnrin Kristi .
Ni ti awon Kristeni eni ami ororo ti Poolu koko kowe si , jije ‘ eru ninu Oluwa ’ kan fifi ami ororo yan won gege bi omo Olorun ati arakunrin Kristi .
Allen àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ máa ń mutí bíi tàwọn tí wọ́n ń wò nínú fíìmù bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ọtí gidi làwọn yẹn ń mu .
Allen atawon ore re maa n muti bii tawon ti won n wo ninu fiimu bo tie je pe ki i se oti gidi lawon yen n mu .
Sísin Jèhófà ni pàtàkì ohun tó máa ń mú kí ẹni tí kò lọ́kọ tàbí ẹni tí kò láya ní ayọ̀ àti ìbàlẹ̀ ọkàn .
Sisin Jehofa ni pataki ohun to maa n mu ki eni ti ko loko tabi eni ti ko laya ni ayo ati ibale okan .
Àwọn tó wà níbẹ̀ sọ èrò wọn nípa ọ̀ràn náà .
Awon to wa nibe so ero won nipa oran naa .
Ahabu bá ranṣẹ pada sí Benhadadi ọba pé, “Mo faramọ́ ohun tí ó kọ́kọ́ bèèrè fún, ṣugbọn n kò lè gba ti ẹẹkeji yìí.”Àwọn oníṣẹ́ náà pada lọ jíṣẹ́ fún Benhadadi ọba.
Ahabu ba ranse pada si Benhadadi oba pe, "Mo faramo ohun ti o koko beere fun, sugbon n ko le gba ti eekeji yii."Awon onise naa pada lo jise fun Benhadadi oba.
Ańgẹ́lì Olúwa sì yọ sí wọn, ògo Olúwa sì ràn yí wọn ká
Angeli Oluwa si yo si won, ogo Oluwa si ran yi won ka
Ṣùgbọ́n ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run pé, bí ẹ̀yin ti jẹ́ ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ rí, ẹ̀yin jẹ́ olùgbọ́ran láti ọkàn wá sí àpẹẹrẹ ẹ̀kọ́ èyí tí Ọlọ́run fi lé yín lọ́wọ́.
Sugbon ope ni fun Olorun pe, bi eyin ti je eru ese ri, eyin je olugboran lati okan wa si apeere eko eyi ti Olorun fi le yin lowo.
Wọ́n kó àwọn ìkòkò, àwọn ọ̀kọ̀, àwọn ọ̀pá tí wọ́n fi ń pa iná lẹ́nu àtùpà, àwọn àwo turari ati àwọn ohun èlò bàbà tí wọ́n máa ń lò fún ìsìn ninu ilé OLUWA.
Won ko awon ikoko, awon oko, awon opa ti won fi n pa ina lenu atupa, awon awo turari ati awon ohun elo baba ti won maa n lo fun isin ninu ile OLUWA.
Ìdí ni pé nígbà táwọn Kristẹni wọ̀nyí wà láyé , irú iṣẹ́ tí Mósè àti Èlíjà ṣe làwọn náà ṣe .
Idi ni pe nigba tawon Kristeni wonyi wa laye , iru ise ti Mose ati Elija se lawon naa se .
Ẹ ó rí àkàṣù ẹ̀kọ mẹ́fà tí mo fi ránṣẹ́ sí yìn, mo sì fi mọ́ìnmọ́ín mẹ́fà tí ẹ o fi jẹ wọn sii.
E o ri akasu eko mefa ti mo fi ranse si yin, mo si fi moinmoin mefa ti e o fi je won sii.
Níbi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ káàkiri àgbáyé , ohun táwọn èèyàn kà sí àìrílégbé yàtọ̀ síra .
Nibi otooto kaakiri agbaye , ohun tawon eeyan ka si airilegbe yato sira .
Ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn ohun míì tí Ọlọ́run dá ló ní “ ọgbọ́n àdámọ́ni ” tí wọ́n ń lò bákan náà láti fi pèsè nǹkan fáwọn ọmọ wọn . — Òwe 30 : 24 .
Opo repete awon ohun mii ti Olorun da lo ni " ogbon adamoni " ti won n lo bakan naa lati fi pese nnkan fawon omo won . -- Owe 30 : 24 .
Nígbà tí ara Ted balẹ̀ díẹ̀ , a pa dà sí orílẹ̀ - èdè Amẹ́ríkà .
Nigba ti ara Ted bale die , a pa da si orile - ede Amerika .
; Galano , L .
; Galano , L .
Ṣé kì í ṣe pé Jóòbù kàn ń tan ara rẹ̀ jẹ ?
Se ki i se pe Joobu kan n tan ara re je ?
Kò sí ẹni tí Ọlọ́run ò ṣe fún, àfi ẹni tó bá ní tòun ò tó.
Ko si eni ti Olorun o se fun, afi eni to ba ni toun o to.
Ohun tí ìwé kan tó ń ṣàlàyé Bíbélì sọ ni pé , “ bí Jésù ṣe fi hàn pé ìlànà ìwà híhù kan náà tó de aya ló de ọkọ rẹ̀ , ṣe ló tipa bẹ́ẹ̀ buyì kún àwọn obìnrin tó sì fi wọ́n sípò iyì . ”
Ohun ti iwe kan to n salaye Bibeli so ni pe , " bi Jesu se fi han pe ilana iwa hihu kan naa to de aya lo de oko re , se lo tipa bee buyi kun awon obinrin to si fi won sipo iyi . "
Ìwé ìṣègùn náà , Merck Manual sọ pé èyí tó tún burú jù bẹ́ẹ̀ lọ ni pé “ ìrora àti ìṣiṣẹ́gbòdì tó máa ń fà fún ara lè sọ èèyàn dẹni tó fi ilé ìwòsàn ṣe ilé , ó sì lè mú kéèyàn máa ṣe bí ẹní fẹ́ para ẹ̀ . ”
Iwe isegun naa , Merck Manual so pe eyi to tun buru ju bee lo ni pe “ irora ati isisegbodi to maa n fa fun ara le so eeyan deni to fi ile iwosan se ile , o si le mu keeyan maa se bi eni fe para e . ”
Ó sì ṣe, bí ó sì ti bẹ̀rẹ̀ sí ní jọba ó pa gbogbo ilé Jéróbóámù, kò sì ku ẹnìkan tí ń mí fún Jéróbóámù, ṣùgbọ́n ó run gbogbo wọn, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa , tí ó sọ nípa ọwọ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ Áhíjà ará Ṣílò
O si se, bi o si ti bere si ni joba o pa gbogbo ile Jeroboamu, ko si ku enikan ti n mi fun Jeroboamu, sugbon o run gbogbo won, gege bi oro Oluwa , ti o so nipa owo iranse re Ahija ara Silo
Díẹ̀ lára àwọn lẹ́tà Glagolitic náà fara hàn bí ìkọ̀wé alákọpọ̀ ti Gíríìkì tàbí Hébérù .
Die lara awon leta Glagolitic naa fara han bi ikowe alakopo ti Giriiki tabi Heberu .
Ọ̀pọ̀ ló ní àwọn ẹrù iṣẹ́ ìdílé .
Opo lo ni awon eru ise idile .
Yẹra fún Ìdẹkùn Ìwà Pálapàla Láàárín Takọtabo
Yera fun Idekun Iwa Palapala Laaarin Takotabo
Nígbà tó bá sì di ọjọ́ iwájú , yóò yọrí sí gbígbádùn ìgbésí ayé nínú ayé kan téèyàn ò ti ní jìyà mọ́ . — Jòhánù 17 : 3 .
Nigba to ba si di ojo iwaju , yoo yori si gbigbadun igbesi aye ninu aye kan teeyan o ti ni jiya mo . — Johanu 17 : 3 .
“Wẹ̀ kí ẹ sì jẹ́ kí ara yín mọ́.Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi!Dáwọ́ àìṣedéédéé dúró,
"We ki e si je ki ara yin mo.E mu iwa ibi yin kuro niwaju mi!Dawo aisedeedee duro,
Retrieved 18 January 2015. ↑ Yoruba Creativity. google.com.ng.
Retrieved 18 January 2015. | Yoruba Creativity. google.com.ng.
Jèhófà bínú , èyí sì yẹ bẹ́ẹ̀ , nítorí náà , ó fawọ́ ààbò rẹ̀ sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn tó ti kẹ̀yìn sí i .
Jehofa binu , eyi si ye bee , nitori naa , o fawo aabo re seyin kuro lodo awon eeyan to ti keyin si i .
□ ní ìgboyà □ gbajúmọ̀ □ wà nínú ẹgbẹ́ kan
# ni igboya # gbajumo # wa ninu egbe kan
nwọn, tí àwọ̀ ara nwọn sì di funfun gẹ́gẹ́bí ti àwọn ará Nífáì;
nwon, ti awo ara nwon si di funfun gegebi ti awon ara Nifai;
Mímọ̀ tí wọ́n mọ̀ pé ìtìlẹyìn àwọn ará wọ̀nyí wà lára ohun tó jẹ́ káwọn lè fàyà rán àwọn ìṣòro náà tún jẹ́ èrè mìíràn .
Mimo ti won mo pe itileyin awon ara wonyi wa lara ohun to je kawon le faya ran awon isoro naa tun je ere miiran .
Bíi ti Ásáfù , irú ẹni bẹ́ẹ̀ kò lè wà ní àlàáfíà pẹ̀lú Ọlọ́run .
Bii ti Asafu , iru eni bee ko le wa ni alaafia pelu Olorun .
Dáfídì tún mọyì àwọn ànímọ́ tí Ọlọ́run fúnra rẹ̀ fi hàn nígbà tí Ọlọ́run “ kọjá níwájú [ Mósè ] ní pípolongo pé : ‘ Jèhófà , Jèhófà , Ọlọ́run aláàánú àti olóore ọ̀fẹ́ , ó ń lọ́ra láti bínú , ó sì pọ̀ yanturu ní inú - rere - onífẹ̀ẹ́ àti òtítọ́ . ’ ”
Dafidi tun moyi awon animo ti Olorun funra re fi han nigba ti Olorun “ koja niwaju [ Mose ] ni pipolongo pe : ‘ Jehofa , Jehofa , Olorun alaaanu ati oloore ofe , o n lora lati binu , o si po yanturu ni inu - rere - onifee ati otito . ’ ”
Àmọ́ , torí pé gbogbo òpin ọ̀sẹ̀ ló fi ń tayò yìí , ó bẹ̀rẹ̀ sí í pa ìpàdé jẹ , kò sì lọ sóde ẹ̀rí déédéé mọ́ .
Amo , tori pe gbogbo opin ose lo fi n tayo yii , o bere si i pa ipade je , ko si lo sode eri deedee mo .
Kí ni ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ tí Jékọ́bù ṣe kó lè wá àlàáfíà pẹ̀lú Ísọ̀ ?
Ki ni ohun to se pataki ju lo ti Jekobu se ko le wa alaafia pelu Iso ?